raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
severe acute respiratory syndrome coronavirus 2 |
tope oshin nigerian television and film director producer and casting director tope oshin je adarí fíìmù ni nàìjíríà ó sì jẹ ìkan laarin awọn gbajúmọ̀ nínú ẹ̀ka eré ni odun 2019 ní ọdún 2015 ìwé ìròyìn pulse sọ wí pé ó wà láàrin àwọn obìnrin mẹsan tí ó ṣe adarí eré tí ó yẹ kí àwọn èèyàn mọ ní ọdún 2018 ní ìrántí oṣù ob... |
kaylah oniwo nigerian media entrepreneur kaylah oniwobíi ni ọjọ́ kẹji lélógún oṣù kìíní je agbóhùnsáfẹ́fẹ́ osere ni nàìjíríà òun ni atọkun ètò the road show àti catwalk with kaylah lóri cool fm ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí kaylah ni oọjọ́ kẹji lélógún oṣù kìíní sì nàìjíríà bàbá rẹ̀ jẹ́ ìkan láàrin àwọn a... |
gbemi olateru olagbegi |
babatunde olatunji |
lalisa manobal lalisa manobal je olorin omo orile-ede tháílàndì |
bàbátúndé ọlátúnjí |
pálánẹ́tì |
patrice talon patrice guillaume athanase talon ọjọ́ìbí 1 may 1958 ni olóṣèlú àti olóṣòwò ará benin tó ti ún ṣe ààrẹ ilẹ̀ benin láti 6 april 2016p ni oṣu kẹsan ọdun 2021 patrice talon ati thomas boni yayi awọn ọrẹ oloselu ti o ti di ọta timọtimọ pade ni aafin marina ni cotonou lakoko tête-à-tête yii thomas boni yayi gbe... |
thomas boni yayi |
joão lourenço joão manuel gonçalves lourenço pípèjao manuel gonsafes lourenso ọjọ́ìbí 5 march 1954 ni olóṣèlú ará angola tó ti wà nípò bíi ààrẹ ilẹ̀ àngólà láti 26 september 2017 tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ ó jẹ́ alákóso ètò àbò ilẹ̀ àngólà láti 2014 dé 2017 ní september 2018 ó di alága ẹgbẹ́ olóṣèlú people's movement for the liberat... |
nana akufo-addo william addo dankwa nana akufo-addo ọjọ́ìbí 29 march 1944 ni ààrẹ ilẹ̀ ghánà lọ́wọ́lọ́wọ́ ó ti wà ní ipò yìí láti 7 january 2017 tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ ó siṣẹ́ bíi agbẹjọ́rò àgbà ilẹ̀ ghánà láti 2001 di 2003 àti bíi alákóso ọ̀rọ̀ òkèrè láti 2003 di 2007 lábẹ́ ìjọba ààrẹ john kufuor |
katerina sakellaropoulou katerina sakellaropoulou gíríkì ọjọ́ìbí 30 may 1956 ni ààrẹ ilẹ̀ gírìsì wọ́n dìbóyán láti dípò ààrẹ prokopis pavlopoulos ní 22 january 2020 látọwọ́ hellenic parliament kú wọn ó tó dìbóyán bíi ààrẹ ilẹ̀ gírìsì ó siṣẹ́ bíi ààrẹ ìgbìmọ̀ iṣẹ́ orílẹ̀-èdè tó jẹ́ ilé-ẹjọ́ òsìṣẹ́ ìjọba ní gírìsì |
ashraf ghani ashraf ghani pashto/ ọjọ́ìbí 19 may 1949 ni olóṣèlú ará afghanístàn tó wà nípò gẹ́gẹ́ bíi ààrẹ ilẹ̀ afghanístàn lọ́wọ́lọ́wọ́ wọ́n kọ́kọ́ dìbòyàn ní 20 september 2014 wọ́n sì tún tún-dìbòyàn ní 28 september 2019 ghani jẹ́ onímọ̀ ìdá-ènìyàn tẹ́lẹ̀ ó siṣẹ́ bíi alákóso ètò ìṣúná àti bíi kánsélọ̀ yunifásítì kab... |
ìmọ̀ àjákálẹ̀-àrùn |
idiat amusu nigerian female engineer idiat aderemi amusu ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó má jẹ́ enginia fún ohun ọ̀gbìn ni nàìjíríà òun sì ni obìnrin àkọ́kọ́ ni ẹgbẹ́ council for the regulation of engineering in nigeria wọn bíi idiat ni ìpínlè kano ni ọjọ́ kẹtàdínlógbon oṣù kọkànlá ọdún 1952 ó wá láàrin àwọn tí ó kọ́kọ́ darapọ... |
moji makanjuola moji makanjuola jẹ́ ogbontarigi oniroyin àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni nàìjíríà òun ni adarí tẹ́lẹ̀ fún ẹgbẹ́ àwọn oniroyin obìnrin ni nàìjíríà nawoj wọ́n bíi moji sì ilẹ̀ kwara ó sì jẹ ìkan laarin awọn oniroyin tí ó dá sí ìgbà sókè ìròyìn ni orílẹ̀ èdè nàìjíríà pàápàá jù lọ ní eka ìròyìn nípa ìlera òun ni olu... |
mercy abang mercy bank abang jẹ́ oniroyin ni nàìjíríà ò gbà ẹ̀bùn nínú ìròyìn ni ọdún 2017 láti ọ̀dọ̀ hammarskjold awards ni united nations ò má ń ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nurọ̀ tí ó pè àkọlé rẹ̀ ni ọ̀rọ̀ pẹ̀lú abang mercy ó sì ti gbà àwọn àlejò bíi rẹno omokri dele momodu àti chude jideonwo ní ọdún 2017 ó gbà ẹ̀bùn woman of t... |
gaston browne gaston alfonso browne ọjọ́ìbí 9 fẹ́ ebruary 1967 ni alákóso àgbà ilẹ̀ antigua ati barbuda òhun ni olórí orílẹ̀-èdè erékùṣù yìí láti ọdún 2014 kó tó di olóṣèlú ó jẹ́ oníṣẹ́ bánkì |
adeola fayehun nigerian journalist adeola eunice oladele fayehun bíi ni ọjọ́ kẹfà oṣù keje ọdún 1984 jẹ́ ọmọ nàìjíríà ó sì jẹ oniroyin tí ó má ń sọ̀rọ̀ nípa àwọn ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ sí àwọn ọmọ ẹ̀yà áfríkà ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí adeola sì nàìjíríà òun sì ni àbíkẹ́yìn nínú àwọn ọmọ márùn-ún tí àwọn òb... |
pope francis |
orílẹ̀-èdè olómìnira ilẹ̀ makẹdóníà |
miguel akọrin miguel jontel pimentel ti a bi ni oṣùu kẹwa ọjọ́ 23 ọdún 1985 jẹ́ akọrin akọ̀wé-orin olóòtú àwo-orin àti òṣeré ará amẹ́ríkà wọ́n tọ́ ọ dàgbà ní san pedro california o bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin nígbà tó tó ọmọ-ọdún mẹ́tàlá lẹ́hìn tó darapọ̀ mọ́ jive records ni ọdún 2007 miguel ṣe àgbéjáde àwo-orin all i want is you... |
àjàkálẹ̀-àrùn covid-19 ní ghánà àwọn ọ̀ran àkọ́kọ́ méjì tí ó jẹmọ́ ajakaye-arun covid-19 ni ilẹ̀ ghana ṣelẹ̀ ní ọjọ́ 12 oṣù kẹwa 2020 nigbati àwọn eniyan meji pada lati nọ́rwèy àti tọ́kì abẹ́lẹ̀ ni ọjọ 12 oṣu kini ọjọ 2020 ajo agbaye fun ilera who fidi rẹ mulẹ pe coronavirus aramada ni fa ti aisan ìmín ninu akopọ àwọn ... |
lola omolola lola omolola bíi ni ọjọ́ kìíní oṣù kẹjọ ọdún 1976 jẹ́ oníróyìn ọmọ nàìjíríà ó dá ẹgbẹ́ obìnrin fin female in kalẹ̀ lórí facebook níbi tí àwọn obìnrin tí sọ àwọn ẹ̀dùn ọkàn wọn ẹ̀kọ́ ó gboyè nínú broadcast journalism láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí columbia college ní chicago iṣẹ́ omolola jẹ́ oníróyìn ó sì ti ṣe atọ... |
krystal okeke krystal okeke jẹ́ oníróyìn àti mọ́dẹ́lì ọmọ nàìjíríà òun ni olùdásílè ẹgbẹ́ america kids multicultural organisation àti miss and mrs america nation beauty pageant ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bíi krystal sì chicago illinois ni orílẹ̀ èdè usa ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ taraba bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ taraba ìyá... |
olóṣèlú olóṣèlú jẹ ènìyàn tí n ṣiṣẹ́ nínú iṣelu ẹgbẹ́ olóṣèlú tàbí ènìyàn tí ó ní tàbí tí ó n wá ipò nínú ijọba awọn oloselu gbero ṣe atilẹyin ati ṣẹda awọn ofin tabi awọn ilana imulo ti o ṣe akoso ilẹ ati nipa itẹsiwaju awọn eniyan rẹ ni fifọ “oloselu” le jẹ ẹnikẹni ti o nwa lati ṣe aṣeyọri agbara iṣelu ni ile-iṣẹ iṣe... |
politician |
lamide akintobi lamidi akintobi jẹ́ oníróyìn àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni nàìjíríà ó sì ṣe gẹ́gẹ́ bíi atọkun ìròyìn lórí channels tv ó ti si ṣé pelu zainab balogun àti ebuka obi-uchendu gẹ́gẹ́ bíi atọkun fún ètò the spot lórí ebonylife tv ìbéèrè pẹpẹ aiyé àti ẹ̀kọ́ rẹ akintobi jẹ́ ọmọ abẹ́òkúta ni ìpínlè ogun ó gboyè b a nín... |
morayo afolabi brown nigerian tv host morayo afolabi-brown jẹ́ olóòtú ètò orí tẹlifíṣọ́ọ̀nù ó ti fìgbà kan jẹ́ olùdarí kejì fún ètò iṣẹ́ ní tvc kí ó tó fiṣẹ́ náà sílẹ̀ ní ọdún 2019 ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olóòtú ètò your view ìgbésí ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ morayo afolabi-brown tí ó jẹ́ gbajúgbajà olóòtú ètò àràárọ̀ your... |
farida waziri farida mzamber waziri tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù keje ọdún 1949 jẹ́ òṣìṣẹ́ agbófinró àti executive chairperson ti economic and financial crimes commission nígbà kan rí òun ló bọ́ sípò náà lẹ́yìn tí nuhu ribadu fi ipò náà sílẹ̀ ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ ọjọ́ keje oṣù keje ọdún 1949 ni a bí farida mzamber waziri ... |
kevin hart kevin darnell hart ọjọ́ìbí july 6 1979 jẹ́ òṣeré aláwàdà àti olóòtú ará amẹ́ríà wọ́n bí ní ìlú philadelphia pennsylvania |
femi robinson femi robinson september 27 1940 may 20 2015 jẹ́ óṣeré fílmù àti tẹlifísàn ará nàìjíríà tó gbajúmọ̀ fún idán rẹ̀ nínú eré tẹlifísàn the village headmaster |
ogun state nigeria |
busta rhymes trevor george smith jr ọjọ́ìbí may 20 1972 tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ orí-ìtàgé rẹ̀ busta rhymes ni olórin rap olórin akọrin olóòtú àwo-orin onígbàjámọ̀ àwọ-orin àti òṣeré ará amẹ́ríkà chuck d láti ẹgbẹ́ olórin rap public enemy ló sọ ọ́ lorúkọ báhun |
trevor george smith jr |
julie coker julie coker jẹ́ akọ̀ròyìn àti akàròyìn ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà nígbà kan rí ó jẹ́ akàròyìn tó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbésí ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ bàbá coker jẹ́ ọmọ yorùbá láti ìlú abẹ́òkúta nígbà tí ìyá rẹ̀ wá láti ẹ̀yà itsekiri ní agbègbè warri ìlú èkó ní ó dàgbà sí tí ó sì ti bẹ̀rẹ̀ ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀... |
charlie parker charles parker jr oṣu kẹjọ ọjọ 29 1920 - oṣu kẹwa ọjọ 12 1955 tí a tún mọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ yardbird tabi lasan bird jẹ afọnfèrè àti olùtòjọ orin jazz ará amẹ́ríkà parker je kan gíga gbajugbaja soloist ati asiwaju olusin ninu idagbasoke ti bebop a fọọmu ti jazz characterized nipa sare tempos virtu... |
ṣèyí ẹdun ṣèyí ẹdun tí àpèjá orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ olúwaṣẹ̀yí ẹdun tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹfà ọdún 4th june jẹ́ gbajúmò òṣèrébìrin sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú ayétòrò ní ìpínlẹ̀ ògùn lórílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni ìyàwó gbajúmọ̀ òṣerékùnrin adéníyì johnson ìgbà èwe àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ṣèyí ẹdun jẹ́ ọmọ bíbí ayétòrò nílẹ̀ ... |
adesuwa onyenokwe adesuwa onyenokwe bíi ni ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹjọ ọdún 1963 jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórí telefisionu ni nàìjíríà ò jẹ́ atọkun ètò fún nta tẹ́lẹ̀ kí ó tó di alatunse fún ìwé ìròyìn tí todays woman òun ni atọkun ètò seriously speaking tí ó jáde ní ọdún 2014 ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí sì ìlú ibada... |
oluremi oyo oluremi oyo bíi ni ọjọ́ kejìlá oṣù kẹwàá ọdún1962 o kú ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 2014 jẹ́ ogbontarigi oníróyìn àti adarí tẹ́lẹ̀ fún ẹgbẹ́ àwọn oniroyin ni nàìjíríà òun ni oluranlọwọ pàtàkì fún olórí orílẹ̀-èdè nàìjíríà ni ọdún 2003 olusegun obasanjo lórí àwọn ọ̀rọ̀ ìkéde òun sì ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó má... |
nancy illoh nancy illoh jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria ó jẹ́ olóòtú ètò moneyshow lórí africa independent television ó sì tún jẹ́ olùdámọ̀ràn media àti alákòóso òwò ilẹ̀ afirika ní daarsat ó jẹ́ alákòóso àgbà ti african economic congress ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ọmọ bíbí ipinle delta ní illoh ó sì jẹ́ àkọ́bí... |
eugenia abu eugenia abu bíi ni ọjọ́ mọ́kàndinlógún oṣù kẹwàá ọdún 1961 jẹ́ oniroyin agbóhùnsáfẹ́fẹ́ akọ̀wé àti akéwì òun ni atọkun ètò ìròyìn tẹ́lẹ̀ fún nigerian television authority nta ó ṣe atọkun ètò lórí nta fún ọdún mẹ́tàdínlọgbọn ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bíi sì ìlú zaria ni ọdún 1962 ó bẹ́ẹ̀rẹ̀ sì... |
aisha falode aisha falode jẹ́ oniroyin fún èrè orí pàápàá ni nàìjíríà òun ní olórí fún ẹgbẹ́ agbaboolu obìnrin fún orílè-èdè nàìjíríà ó wá láàrin àwọn òṣìṣẹ́ tí ó kọ́kọ́ bẹẹ rẹ̀ ní ilé iṣẹ́ telefisionu tí african independent television ó ti si ṣé pelu nigerian telecommunication limited àti graduate telephone operators ... |
isioma daniel nigerian journalist isioma nkemdilim nkiruka daniel bíi ni 1981 jẹ́ oniroyin ọmọ nàìjíríà ó fi èsì sì ìròyìn nípa obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni àgbáyé èyí ló fà tí àwọn kí àwọn mùsùlùmí fi sọ wípé kí wọn pá isioma lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí university of central lancashire níbi tí ó tí gboyè nínú ìròyìn àti òṣèl... |
abike dabiri abike kafayat olúwa toyin dabiri-erewa jẹ́ òṣèlú àti ọmọ ẹgbẹ́ tẹ́lẹ̀ fún nigeria federal house of representatives òun sì ni aṣojú fún ìlú ìkoròdú tí ìpínlẹ̀ èkó níbẹ̀ òun ni alága tẹ́lẹ̀ fun ìgbìmò ìkéde àti media òun sì ní alága tẹ́lẹ̀ fún ìgbìmò diaspora affairs ní ọdún 2015 ó di oluranlọwọ pàtàkì àgbà ... |
lola akinmade åkerström lola akinmade jẹ ayàwòrán àti akọ̀wé ọmọ nàìjíríà òun ni alatunse fún ilé iṣẹ́ slow travel stockholm àwọn iṣẹ́ rẹ tí farahàn nínú national geographic traveler bbc àti cnn ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ó gbé ní èkó ni nàìjíríà nígbà di ìgbà tí ó pè ọmọ ọdún mẹẹdogun tí ó wà fi lọ sí orílẹ̀ ... |
amarachi nwosu amarachi nwosu bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógbọ̀n oṣù kẹ̀sán ọdún 1994 jẹ́ ayàwòrán eléré àti akọ̀wé ó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà òun ni oludasile melanie unscripted eré ìtàn black in tokyo tí ó ṣe tí farahàn ni international centre of photography ni ọdún 2017 ni ìlú new york ó sì tí farahàn ni ultra super new galle... |
muma gee muma gee née uwame bi 18 november 1978 agbejoro mọ bi muma gee /m u m ə dʒ mo / afipamo ṣe rere gift ni a nigerian singer-silẹ oṣere businesswoman njagun onise tẹlifisiọnu eniyan ati oloselu a bi i o dagba o si gbe ni port harcourt itọwo akọkọ ti uwame ti stardom wa nipasẹ orin rẹ kade eyiti o di orin akọle ak... |
prince buster cecil bustamente campbell 24 may 1938 8 september 2016 tó gbajúmọ̀ bíi prince buster jẹ́ akọrin akọ̀wé-orin àti olóòtú ará jamáíkà àwọn orin rẹ̀ ní ìgbà àwọn ọdún 1960 ló ṣe ìpilẹ̀sẹ̀ orin ayéòdeòní ilẹ̀ jamáíkà |
cecil bustamente campbell |
hitoshi ogawa hitoshi ogawa 小河等 ogawa hitoshi february 15 1956 may 24 1992 jẹ́ awakọ̀sáré ará ilẹ̀ japan |
uhuru kenyatta uhuru muigai kenyatta ọjọ́ìbí 26 october 1961 ni olóṣèlú onísòwò àti ààrẹ orílẹ̀-èdè olómìnira ilẹ̀ kẹ́nyà kẹrin lọ́wọ́lọ́wọ́ |
ààrẹ ilẹ̀ kẹ́nyà ààrẹ orílẹ̀-èdè olómìnira ilẹ̀ kẹ́nyà <ns>10</ns> <id>12795</id> <revision> <id>534721</id> <parentid>473798</parentid> <timestamp>2020-05-23t231720z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> ni olórí orílẹ̀-èdè... |
president of kenya |
ozak esu ozak-obazi oluwaseyi esu tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹrin ọdún 1991 tí ń ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ electrical engineer tí ó sì jẹ́ adarí ní building research establishment centre for smart homes and buildings cshb ó ti fìgbà kan ṣiṣẹ́ ní cundall ní birmingham níbi tí wọ́n ti ń ṣẹ̀dá ohun ìkọ́lé ... |
nike folayan dr nike folayan mbe tí a bí ní ọdún 1978 jẹ́ chartered engineer àti telecommunications engineering consultant ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ àti alága fún association for black and minority ethnic engineers tí ó ń kéde ethnic diversity nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ ní uk ètò-ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ rẹ̀ folayan gboyè meng nínú e... |
lauryn hill lauryn noelle hill ọjọ́ìbí may 26 1975 ni akọrin akọ̀wé-orin àti olórin rap ará amẹ́ríkà tó jẹ́ ìkan nínú ọmọ ẹgbẹ́ olórin rap fugees àti fún àwo-orin tó dá gbé jáse tó ún jẹ́ the miseducation of lauryn hill tó gba ẹ̀bùn ọ̀pọ̀lọpọ̀ tó sì léwájú ọ̀pọ̀ rẹ́kọ́rdù ìtajà àwo-orin hill ni ìkan nínú àwọn olórin ra... |
octavia spencer octavia lenora spencer ọjọ́ìbí may 25 1972 ni òṣeré olùkọ̀wé àti olóòtú ará amẹ́ríkà igbesi aye arabinrin naa octavia lenora spencer ni a bini montgomery alabama ti o sini awọn aburo mẹfa lara wọn ni rosa ati areka spencer iya óṣèrè lobinrin naa dellsena spencer 1945-1988 ṣiṣẹ gẹgẹbi ọmọ ọdọ baba arabin... |
cleopatra tawo cleopatra tawo tí orúkọ inagi rẹ jẹ cleo tao jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórí rádíiò ni ilé iṣẹ́ planet fm 1011 fm ni ìlú uyo ni ìpínlẹ̀ akwa ibom òun ni atọ́kun ètò day break on planet àti automania kí ó tó darapọ̀ mọ́ planet fm tawo tí si ṣé pẹ̀lú rythm fm 937 ni ìlú portharcourt ni ìpínlẹ̀ rivers gẹ́gẹ́ bíi a... |
betty abah betty abah bíi ni ọjọ́ kẹfà oṣù kẹta ọdún 1974 jẹ́ oníróyìn akọ̀wé àti ajíjágbara fún àwọn ọmọdé àti àwọn obìnrin òun ni olùdásílẹ̀ àti adarí fún cee hope ní ìlú èkó ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí betty sí ìlú otukpo ní ìpínlẹ̀ benue ó gboyè nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ èdè gẹ̀ẹ́sì láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí uni... |
màlúù màlúù takọ tabo ni wọ́n wọ́pọ̀ láàrin àwọn ẹranko ọ̀sìn ilé wọ́n jẹ́ ọ̀kan lára ìsọ̀rí ẹbí àwọn ẹranko tí a mọ̀ sí bovinae tí wọ́n wọ́pọ̀ ju màlúù kẹ̀tẹ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ìwúlò màlúù wọ́n sábà ma ń rè tàbí sin màlúù gẹ́gẹ́ bí ohun ọ̀sìn fún jíjẹ pípèsè ẹran fífi awọ rẹ̀ ṣe pànmọ́ ohun tí a lè fi pèsè wàrà wọ́n ... |
ṣọ̀ún ìlú ògbómọ̀sọ́ ṣọ̀ún ìlú ògbómọ̀sọ́ tàbí ṣọ̀ún ògbómọ̀ṣọ́ lásán jẹ́ orúkọ oyè ọba aládé tí ìlú ògbómọ̀ṣọ́ ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ọba ọládùnǹní oyèwùnmí iii ní ó wà lórí ìtẹ́ ṣọ̀ún tí ògbómọ̀ṣọ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ ó gorí ìtẹ́ àwọn babańlá baba rẹ̀ lọ́jọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹwàá ọdún 1973 |
seyi shay deborah oluwaseyi joshua bí ni ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kejìlá ọdún 1985 tí orúkọ inagi rẹ jẹ́ seyi shay jẹ́ olórin akọrin àti òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó kọ orin tí wọn lò fún crime lifegang wars ni ọdún 2005 ní oṣù kọkànlá ní ọdún 2013 ó gbà iṣẹ́ láti ọ̀dọ̀ etisalat ní oṣù keje ọdún 2015 ó darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ... |
ṣọ̀ún ti ògbómọ̀sọ́ |
ọba ìlú èkó ọba ìlú èkó ni atáyéṣe átọwọ́dọ́wọ́ olórí ìlú èkó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ọba ìlú èkó lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ọba rilwan akiolu tó dípò ọba adeyinka oyekan kejì tó ṣe aláìsí ní ọdún 2003 |
rilwan akiolu |
cattle |
àmọ̀tẹ́kùn fún ẹranko tí yorùbá ńpè ní àmọ̀tẹ́kùn ẹ wo ojú ewé ẹkùn panthera pardus ni ìkan nínú àwọn irú ẹranko márùn tó wà láyé nínú ìbátan panthera ìkan nínú àwọn ẹ̀dá-olóngbò ó pọ̀ káà kiri ní agbègbè ìsàlẹ̀-sàhárà áfríkà ní àwọn agbègbè kan ní apá ilàòrùn àti arin asia ní ìsàlẹ̀orílẹ̀ india dé apá gúúsù-ìlàòrùn àt... |
leopard |
taiye selasi taiye selasi bíi ni ọjọ́ kẹji oṣù kọkànlá ọdún 1979 jẹ́ akọ̀wé àti ayàwòrán ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí taiye sì ìlú london òun sì ni àkọ́bí nínú ìbejì tí àwọn òbí rẹ bí ìyá rẹ̀ dr juliette tuakli jẹ́ oníṣègùn ni orílẹ̀ èdè ghana bàbà rẹ dr lade wosornu sì jẹ́ dókítà ni ilẹ̀ saudi arabia ta... |
list of presidents of rwanda |
àtòjọ àwọn ààrẹ ilẹ̀ rùwándà àyọkà yìí ṣe àtòjọ orúkọ àwọn ààrẹ ilẹ̀ rùwándà láti ìgbà tí wọ́n dá ipò náà sílẹ̀ ní ọdún 1961 nígbà ìjídìde àwọn ará rùwándà títí di òní gẹ́gẹ́ bí òfin-ìbágbépọ̀ ṣe lànà rẹ̀ iṣẹ́ ààrẹ ni gẹ́gẹ́bí olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ rwanda ó sì ní agbára aláṣe tó pọ̀ wọ́n dìbò yan sí ipò ààrẹ yìí fún ọd... |
list of presidents of rwanda |
adama barrow adama barrow ọjọ́ìbí 16 february 1965 ni olóṣèlú ará gambia àti agbalékọ́ tó jẹ́ ààrẹ ilẹ̀ gámbíà kẹta lọ́wọ́lọ́wọ́ lórí àga láti ọdún 2017 ni oṣu kọkanla ọdun 2021 adama barrow kede ipo oludije rẹ fun idibo alakoso 2024 |
òṣèlúaráìlú |
head of state |
olórí orílẹ̀-èdè olórí orílẹ̀-èdè ni ẹni aráàlú kan tí óún dúró fún orílẹ̀ ìjọba kan lábẹ́ àṣẹ ní ìṣọ̀kan àti lábẹ́ òfin rẹ̀ bí irú ìjọba àti ìpín àwọn agbára ìjọba orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan bá ṣe rí olórí orílẹ̀-èdè le jẹ́ fún oyè lásán tàbí lẹ́ẹ̀kannáà bíi olórí ìjọba àti ìṣẹ́ míràn |
wàrà wàrà ni ohun mímu funfun olómi tí ó ní èròjà aṣara lóore tí a ma ńnfún láti ẹnu ọmú màlúù tí ó sì jẹ́ ìpìlẹ̀ èròjà ìdàgbà-sókè fún ọmọ màlúù tí ó bá ń mumú àti ọmọ ènìyàn pàá pàá kí wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ sí jẹun nínú wàrà ni kolósítírọ́ọ̀mù tí ó jẹ́ èròjà aṣara-lóore gan an sodo sí nígbà tí èyíkéyí ẹranko alégun lẹ́yìn a... |
mokgweetsi masisi mokgweetsi eric keabetswe masisi ọjọ́ìbí 21 july 1961 ni ààrẹ ilẹ̀ bòtswánà ìkárùn lọ́wọ́lọ́wọ́ láti ọdún 2018 ó jẹ́ alákóso ètò ẹ̀kọ́ tẹ́lẹ̀ àti alákóso ọ̀rọ̀ iṣẹ́ ààrẹ àti ìmójútó ìgboro láti 2011 di 2014 wọ́n kọ́kọ́ dìbò yàán sí ilé-aṣòfin ní 2009 |
president of botswana |
ààrẹ ilẹ̀ bòtswánà ààrẹ orílẹ̀-èdè olómìnira ilẹ̀ bòtswánà ni olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba ilẹ̀ bòtswánà bákanáà ó tún jẹ́ aláṣẹ àgbà ilé-ìṣẹ́ ológun nílànà bí òfin-ìbágbépọ̀ ilẹ̀ bòtswánà ṣe sọ ìgbà àsìkò ayé àwọn ààrẹ ilẹ̀ bòtswánà this is a graphical lifespan timeline of presidents of botswana the presidents are... |
félix tshisekedi félix antoine tshisekedi tshilombo ọjọ́ìbí 13 june 1963 ni olóṣèlú ará kóngò tó ti jẹ́ ààrẹ orílẹ̀-èdè olómìnira òṣèlú ilẹ̀ kóngò láti 25 january 2019 |
orílẹ̀-èdè olómìnira olóṣèlú ilẹ̀ kóngò |
betty shabazz betty shabazz orúkọ àbísọ betty dean sanders may 28 1934 june 23 1997 tí a tún mọ̀ bákannáà bíi betty x jẹ́ olùkọ́ àti alákitiyan àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú ará amẹ́ríkà shabazz ni ìyàwó malcolm x |
iwe iwe jẹ́ ẹ̀yà ara kan tí iṣẹ́ rẹ̀ dá lórí lílọ̀ oúnjẹ tí a jẹ nínú tí ó ti dà nínú púpọ̀ ẹranko ẹ̀yà ara yí jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú ara ìrísí rẹ̀ iwe rí roboto tinú tẹ̀yìn rẹ̀ jẹ́ kìkì iṣan tí ó sì ma ń lọ óúnjẹ pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ àwọn òkúta wẹ́wẹ̀wẹ́ |
iwe gizzard |
àpáta àpáta jẹ́ ohun ribiti tí ó ń ṣẹlẹ̀ fúnra rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ohun àlùmọ́nì àpáta pín sí ọìsọ̀rí mẹ́ta pàtàkì jùlọ àwọn ni igneous rocks metamorphic rocks àti sedimentary rocks àpáta jẹ́ ohun tí ó fojú han jùlọ ní orí-ilẹ̀ ẹ̀ka ìmọ̀ tí a ti ń kọ́ nípa àpáta ìrúsókè ati àtòjọ rẹ̀ ni wọ́n ń pè ní petrology ní èyí tí ó sì ... |
apáta |
irì irì erì enini tabí nini jẹ́ omi kan tí ó ma ń sẹ tàbí kóra jọ sí orí ewé koríko tàbí ohun kan mìíràn tí ó bá wà ní abẹ́ sánmọ̀ ní òru mọ́jú tàbí lásìkò tí ojú ọjọ́ bá bora ohun tí ìmọ̀ fún múlẹ̀ ni wípé nígbà tí oru tàbí ìgbóná ojú ọjọ́ bá ń bora tí afẹ́fẹ́ tutù ń fẹ́ oru ara àwọn ewéko àti àwọn ohun mìíràn tó ti g... |
ewé ewé jẹ́ àkójọ pọ̀ orúkọ fún àwọn ẹtúntún igi oríṣríṣi tí a lè fojú rí ìrísí rẹ̀ ewé jẹ́ ohun tí ó ma ń sába rí pẹlẹbẹ ó ma ń ní ilà tẹ́ẹ́rẹ́ láàrin bí ìṣẹ̀dá igi kọ̀ọ̀kan bá ṣe rí ni ewé rẹ̀ ṣe ma ń falà sára ewé sábà m ń hù sí ara tabí orí igi lọ́pọ̀ ìgbà èyí náà tún dá lé irúfẹ́ ìṣẹ̀dá igi kọ̀ọ̀kan híhù igi sára ... |
ìjìnnà-síra-ẹni láwùjọ nínú ètò ìlera àwùjọ ìjìnnà-síra-ẹni láwùjọ ìjìnnà-síra-ẹni lójúkojú jẹ́ ìlànà tí kìí ṣe nípa ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ìlò oògùn pẹ̀lú èròǹgbà láti dènà títànká àjàkálẹ̀ ààrùn nípa jíjìnnà sí ara ẹni lójúkojú láti ṣe àdínkù iye ìgbà tí àwọn ènìyàn lè súnmọ́ ara wọn pẹ́kípẹ́kí ó jẹ mọ́ ìṣèdiwọ̀n bí ènìyàn kan... |
sánmọ̀ sánmọ̀ tabí ojú ọ̀run jẹ́ gbogbo ohun tí ó wà lókè ilẹ̀ níbi tí ohun bí kùrukùru oòrùn òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀ ti ń yọjú wo ilẹ̀ lásìkò ìkọ̀ọ̀kan wọn ní inú ìmọ̀ ojú-ọ̀run sánmọ̀ yí ni wọ́n ń pè ní ahòho níbi tí oòrun òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀ ti dàbí ẹni wípé wọ́n ń rọ̀ kiriká ọ̀run fúra rẹ̀ní ọ̀gangan ilẹ̀ ọ̀nà tí s... |
ọmú ọmú tàbí ọyàn jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú ẹ̀yà ara tí ó wà lọ́wọ́ òkè lára àwọn obinrin ó jẹ́ ẹ̀yà tí ó ma ń sun wàrà gẹ́gẹ́ bí óúnjẹ fún àwọn ọmọ ọwọ́ tí wọ́n ń mumú tọkùnrin tobìnrin ní wọ́n ma ń ní ọmú ní àyà wọn àmọ́ ní àsìkò ìbàlágà ẹ̀yà ara yí ma ń dàgbà sókè lára abo látàrí èròjà ara tí wọ́n ń pè ní estrogen àti g... |
àdéhùn igi aláwọ̀-ewé àdéhùn igi aláwọ̀-ewé ní ìwé àdéhùn ìpẹ̀tùsáwọ̀ ìjà ilẹ̀ tí ó kún fún epo-rọ̀ ì àti afẹ́fẹ́ gáàsì ẹnubodè láàárín orílẹ̀ èdè cameroon àti nàìjíríà tí wọ́n ń pè ní bakassi 1981 ìjàkú-akátá àwọn ọmọ-oogun láàárín nàìjíríà àti cameroon lọ́dún 1994 àti 1996 wáyé ní bakassi wọ́n gbé aáwọ̀ ìjà yìí lọ sí... |
ọ̀gbàrá nínú ìmọ̀ sáyẹ́nsì nípa ilẹ̀ ọ̀gbàrá jẹ́ wíwọ́ omi àrọ̀dá òjò tí ṣẹ̀ṣẹ̀ rọ̀ tán tí ó sì nń wọ́ yanrìn tàbí iyẹ̀pẹ̀ orí ilẹ̀ lọ bí òun náà ṣe ń wọ́ ruru láti ibìkan sí òmíràn àkíyèsí ọ̀gbàrá yàtọ̀ sí fífọ́n òjò kí a má ṣìí gbé síra wọn torí fífọ́n òjò kìí ṣàngbàrá ṣíṣàn ọ̀gbàrá tún jẹ́ ìṣe àdámọ́ ítí láé láé àwọ... |
fally ipupa fally ipupa n'simba ọjọ́ìbí december 14 1977 tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìtàgé rẹ̀ fally ipupa ní akọrin-akọ̀wéorin oníjó ọlọ́rẹ onígìtá àti olóòtú ará kóngò láti ọdún 1999 dé 2006 ó jẹ́ ìkan nínú ẹgbẹ́ olórin quartier latin international tí koffi olomidé dásílẹ̀ ní 1986 |
olúṣọlá ìṣọ̀lá ògúnṣọlá olúṣọlá ìṣọ̀lá ògúnṣọlá tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí isho pepper ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kọkanlá ọdún 1942 sí ìdílé ọ̀gbẹ́ni sámúẹ́lì ògùnṣọlá ní agbolé baàlà dáṣàolú lẹ́yìn mọ́sálásí ìta ìgbẹ̀yìn ládùúgbò òkè ìtokú ní ìlú abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ ògùn ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ olúṣọlá gẹ́gẹ́ bí àbígbẹ̀yìn nín... |
muhammad |
mùhọ́mádù mùhọ́mádù tàbí muhammad lárúbáwá c 570 ce 8 june 632 ce jẹ́ olórí ẹ̀sìn àwùjọ àti olóṣẹ̀lú áràbù àti olúdásílẹ̀ ẹ̀sìn ìmàle |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.