raw_text
stringlengths
2
128k
richard ihetu
katherine jackson katherine esther jackson née scruse orúkọ àbísọ kattie b screws may 4 1930 ni ìyá-àgbà ìdílé jackson òhun ni ìyá michael àti janet jackson àti àwọn ẹ̀gbọ́n wọn
joe jackson manager
joe jackson joseph walter jackson july 26 1928 june 27 2018 je monija olorin ara amerika ati baba-agba idile jackson ohun ni baba michael ati janet jackson won fi oruko re sinu ile awon olokiki rhythm and blues ni 2014
oleta adams oleta adams ojoibi may 4 1953 jẹ̀ akọrin ẹ̀mí àti àti atẹdùùrù ará amẹ́ríkà tó gbajúmọ̀ fún agbára ohùn rẹ̀ ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayẹ́ rẹ̀ adams tí wón bí gẹ́gẹ́ bí ọmọbìnrin si ajíhìnrere ti o si dàgbà sí gbígbọ́ orin ẹ̀mí nígbà tí o dàgbà awọn ẹbí rẹ̀ kólọ sí yakima washington ó bẹ̀rē orin kíkọ ni sọ́ọ́sì kí ó tó...
juan martín del potro orúkọ yìí lo àṣà ìṣorúkọ ní èdè spéìn àkọ́kọ́ tàbí orúkọ ìdílé bàbá ni del potro èkejì tàbí orúkọ ìdílé ìyà ni lucas juan martín del potro lucas ọjọ́ìbí 23 september 1988 tàbí delpo jẹ́ agbá tẹ́nìs ará argentina tó wà ní ipò no 122 lágbàyé ní tẹ́nìs àwọn ọkùnrin ẹnìkan association of tennis profes...
bianca andreescu bianca vanessa andreescu ọjọ́ìbí june 16 2000 ni agbá tẹ́nìs ará kánádà ipò rẹ̀ lágbààyé tó gajùlọ ni no 4 òhun ni ará kánádà tí ipò rẹ̀ gajùlọ láti ìbẹ̀rẹ̀ àjọ women's tennis association wta andreescu gba ife-ẹ̀yẹ open amẹ́ríkà 2019 àti ife-ẹ̀yẹ open kánádà 2019 nígbà tó borí serena williams ní ìparí ...
sofia kenin sofia anna kenin pẹ̀lú ìnagijẹ sonya ọjọ́ìbí november 14 1998 ni agbá tẹ́nìs ará amẹ́ríkà ipò rẹ̀ tógajùlọ láàgbáyé àjọ women's tennis association wta ni no 4 kenin gba ife-ẹ̀yẹ open australi 2020 nígbà tó borí garbine muguruza ní ìparí ìdúje náà èyì sọ ọ́ di ọ̀dọ́mọdé kékeré jùlọ ará amẹ́ríkà tó gba ìdíje ...
jeļena ostapenko jeļena ostapenko ọjọ́ìbí 8 june 1997 wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi aļona ostapenko ni agbá tẹ́nìs ará latvia ipò wta rẹ̀ láàgbáyé tó gajùlọ ni no 5 nínú àwọn ìdíje ẹnìkan tó dé bẹ̀ ní 19 march 2018 àti no 17 nínú àwọn ìdíje ẹnimẹ́jì tó dé bẹ̀ ní 2 march 2020 ostapenko gba ife-ẹ̀yẹ open fránsì odun 2017 nígbà tó b...
omijé omijé jẹ́ omí kan tó mọ́ kangá tóma ń sun jáde láti inú ibùsun kan tó wà nínú ihò ojúa lè ṣalábàápàdé omi yí ní ara gbogbo ẹranko afọ́nọlọ́nú tókù yàtọ̀ ewúrẹ́ àti ehoro kókó iṣẹ́ omijé ọmọnìyàn nìkan ni ó ma ń fi ìmọ̀sí-lára rẹ̀ hàn pẹ́lú sísun omijé lójú nígbà ayọ tàbí ìbànújẹ́ omijé tún jẹ́ àmì kan pàtàkì láàr...
àwọn obìnrin lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ women in niger ipa tí àwọn obìnrin lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ń kó láwùjọ yàtọ̀ lóríranǹran nípa ọ̀rọ̀ ajẹmọ́ ẹ̀sìn àti àgbègbè tí wọ́n bá wà ipa pàtàkì tí a mọ̀ mọ àwọn obìnrin ni ipa gẹ́gẹ́ bí ìyá ẹ̀gbọ́n tàbí àbúrò obìnrin àti ìyàwó ní àfikún ipa obìnrin nígbà mìír...
lynn whitfield lynn whitfield orúkọ ìdílé butler-smith ọjọ́ìbí february 8 1953 ni òṣeré àti olóòtú ará amẹ́ríkà whitfield bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìṣeré rẹ̀ ní orí tẹlifísàn àti tíátà kó tó bẹ̀rẹ̀ sí ní seré nínú fílmù ó gba ẹ̀bùn primetime emmy kan wọ́n sì pè é lórúkọ fún ẹ̀bùn golden globe fún idọ́n rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi josephine baker...
jim hanks james mathew jim hanks june 15 1961 je osere ara amerika
antonio fargas antonio juan fargas ọjọ́ìbí august 14 1946 ni òṣeré ará amẹ́ríkà tó gbajúmọ̀ fún àwọn ìṣeré rẹ̀ nínú àwọn fílmu blaxploitation ní ìgbà 1970 àti fún ìṣeré rẹ̀ bíi huggy bear nínú eré tẹlifísàn ìgbà 1970 starsky hutch ìgbà èwe wọ́n bí fargas ní ìlú new york sí mildred orúkọ ìdílé bailey àti manuel fargas ó...
trinidad àti tobago
ben chijoke ty ben chijioke tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ ty ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1972 tí ó sìn ṣaláìsí lọ́jọ́ keje oṣù karùn-ún ọdún 2020 17 august 1972 7 may 2020 jẹ́ olórin tàkasúfèé lórílẹ̀-èdè gẹ̀ẹ́sì ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó ṣe àwo orin tí ó pe àkọlé rẹ̀ ní awkward...
ọba ọlátẹ́rù ọlágbègí ii ọba ọlátẹ́rù ọlágbègí ii tí wọ́n bí ní oṣù kẹjọ ọdún 1910 tí ó sìn di olóògbé lọ́dún 1998 august 1910 - 1998 jẹ́ ọba ọlọ́wọ̀ ti ìlú ọ̀wọ̀ nílẹ̀ yorùbá ọ̀wọ̀ jẹ́ olú ìlú àtijó fún apá ìlà òòrùn ilẹ̀ yorùbá lórílẹ̀ èdè nàìjíríà wọ́n yàn án sípò ọba ọ̀lọ́wọ̀ tìlú ọ̀wọ̀ lọ́dún 1941 ó jọba fún ọdún ...
ojúọ̀nà ip
ip address
internet protocol
ọba ọlátẹ́rù ọlágbèmí ii
olateru olagbegi
samuel ládòkè akíntọ́lá
little richard richard wayne penniman december 5 1932 may 9 2020 tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìnagijẹ little richard jẹ́ akọrin akọ̀wé-orin àti olórin ará amẹ́ríkà gẹ́gẹ́ bíi ènìyàn pàtàkì nínú orin alásìkí àwọn iṣẹ́ orin richard bẹ̀rẹ̀ ní ìgbà àrin àwọn ọdún 1950 nígbà tí agbára orin àti ìdán orin rẹ̀ ṣe ìpilẹ̀sẹ̀ fún orin...
richard wayne penniman
bennet omalu bennet ifeakandu omalu ọjọ́ìbí september 30 1968 ni oníṣègùn onímọ̀ ìwadí àìsàn ikú-aláìsí àti onímọ̀ àìsàn iṣan-ìkanra ọmọ nàìjíríà amẹ́ríkà tó kọ́kọ́ já ọgbọ́n àti ẹni tó kọ́kọ́ kọ ìwé ìwádìí lórí àìsàn inú-opọlọ ìforígbá léraléra cte ní àrin àwọn agbábọ́ọ̀lù amẹ́ríkàn futúbọ̀lù nígbà tó ún siṣẹ́ ní ilé-...
idemili south
ìlú new york
nigerian americans
àwọn ọmọ nàìjíríà amẹ́ríkà àwọn ọmọ nàìjíríà amẹ́ríkà nigerian americans ní àwọn ará amẹ́ríkà tí wọ́n ní ìbátan mọ́ ará nàìjíríà ìdíye tí american community survey ṣe ní ọdún 2016 sọ pé àwọn ará ìlẹ̀ amẹ́ríkà tí wọ́n pe ara wọn ní ọmọ nàìjíríà tó 380785 nínú wọn àwọn 277027 ni wọ́n bí ní nàìjíríà nigeria is both the mo...
american football
amẹ́ríkàn futbọ́ọ̀lù amẹ́ríkàn futbọ́ọ̀lù tàbí bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ amẹ́ríkà ni eré-ìdárayá tó gbajúmọ́ ní orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà àti kánádà ó jẹ́ eré-ìdárayá ẹlẹ́gbẹ́mẹgbẹ́
enugwu ukwu enugwu ukwu english on top of a high hill ni ìlú kan ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ njikoka ní ìpínlẹ̀ anambra nàìjíríà
pittsburgh pittsburgh ni ìlú kan ní ìpínlẹ̀ pennsylvania ní orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà àti ìbùjóòkó ìjọba ìbílẹ̀ allegheny county
ìpínlẹ̀ pennsylvania
epidemiology
ìmọ̀ àjàkálẹ̀-àrùn ìmọ̀ àjàkálẹ̀-àrùn ni ẹ̀kọ́ àti ọ̀nà ìgbékalẹ̀ àti ìgbéyẹ̀wò bí àrùn ṣe ń tàn kálẹ̀ láàrín àwọn ènìyàn ó tún jẹ́ ọ̀nà ìwádìí àrùn àti ohun ń fa àjàkálẹ̀ àrùn ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ilé-iṣẹ́ ìjọba tó ń mójútó ìbẹ́sílẹ̀ àjákálẹ̀-àrùn ni nigeria centre for disease control
columbia university
yunifásítì kòlúmbíà yunifásítì kòlúmbíà bákanáà bíi kòlúmbíà àti fún ìṣeṣẹ́ bíi columbia university in the city of new york ni is a yunifásítì aṣèwadìí aládàníi ivy league ní new york city wọ́n da sílẹ̀ ní ọdún 1754 lórí ilẹ̀ trinity church ní manhattan kòlúmbíà ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga tó pẹ́ jùlọ ní ìpínlẹ̀ new york àti èyí...
new york state
joana maduka nigerian female engineer joana olu maduka bíi ni ọjọ́ kẹfa oṣù karùn-ún ọdún 1941 jẹ́ onímọ̀ iṣẹ́-ẹ̀rọ ará ilẹ̀ nàìjíríà ó jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ tí ó má dára pọ mọ ẹgbẹ́ council for the regulation of engineering in nigeria coren institution of electrical engineers nigerian society of engineers àti nigerian a...
stephanie coker stephanie omowunmi eniafe coker bíi ọjọ́ kejìdínlógbon oṣù kọkànlá ọdún 1988 jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ àti olùdarí ètò lórí telifisoonu fún mtv base africa àti ebony life tv' ó kópa nínú eré gbajúmò tinsel' = ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ = wọn bí stephanie sì ipinle eko ni orile ede nàìjíríà ṣùgbọ́n ó ...
tlc tlc ni ẹgbẹ́ olórin obìnrin ará amẹ́ríkà tí ọmọ ẹgbẹ́ jẹ́ tionne t-boz watkins lisa left eye lopes àti rozonda chilli thomas wọ́n dáa sílẹ̀ ní ìlú atlanta georgia ní ọdún 1991 ẹgbẹ́ náà yọrí sí rere ní ìgbà àwọn ọdún 1990s wọ́n ṣe orin mẹ́sàn tó bọ́ sí top-ten hits lórí billboard hot 100 nínú wọn ni mẹ́rin tó bọ́ s...
gríìsì
usher usher raymond iv ọjọ́ìbí october 14 1978 ni akọrin akọ̀wé-orin òṣeré àti oníjó ará amẹ́ríkà wọ́n bi ní dallas texas sùgbọ́n ó dàgbà ní chattanooga tennessee kó tó kó lọ sí atlanta georgia
muna rapper munachi gail teresa abii nwankwo jẹ́ olórin akọrin agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórí telefision àti osere ni ìpínlè nàìjíríà ó gbé ìgbà o ròkè nínú ìdíje obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni nàìjíríà ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ imo ni nàìjíríà = ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ = wọn bíi sì ilẹ̀ port harcourt ibẹ̀ ni ó sì gbé dàgbà ó lọ ...
taiwo ajai-lycett taiwo ajai-lycett bíi ọjọ́ keta oṣù kejì ọdún 1941 ni òṣeré oníròyìn àti atọ́kùn ará ilẹ̀ nàìjíríà ajai-lycett ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó ṣe iṣẹ́ olóòtú ìwé-ìròyìn africa woman ni ọdún 1970 ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọn bí lycett ni ọjọ́ keta oṣù kejì ọdún 1941 ni ìpínlè èkó bàbà rẹ jẹ ọmọ ìran...
antelope
ẹtu ẹtu ni à ún pe orísirísi àwọn ẹranko ajẹnu oníka-dídọ́gba tó jẹ́ abínibí sí orísi agbègbè ní áfríkà àti eurasia
ving rhames irving rameses rhames ọjọ́ìbí may 12 1959 ni òṣeré tìátà àti fílmù ará amẹ́ríkà
kim fields kim victoria fields ọjọ́ìbí may 12 1969 ni òṣeré àti olúdarí ètò tẹlifísàn ará amẹ́ríkà fields gbajúmọ̀ fún ìseré rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi dorothy tootie ramsey nínú eré aláwàdà ilé-iṣẹ́ tẹlifísàn nbc the facts of life 19791988 àti gẹ́gẹ́ bíi regine hunter nínú eré aláwàdà ilé-iṣẹ́ tẹlifísàn fox living single 19931998...
adaora onyechere adaora onyechere jẹ́ oniroyin oníṣòwò akéwì àti onkọ̀we ni ìlẹ̀ nàìjíríà òun sì ní atọkun ètò tẹ́lẹ̀ fún ètò kakaaki lórí africa independent television òun sì ní atọkun ètò talk 2 adaora lórí kiss fm ni gbogbo ọjọ́ ìṣẹ́gun ní ago mẹrin ìrọ̀lẹ́ òun ni oludasile ẹgbẹ́ women enabling women everywher wewe ...
enya enya oruko abiso eithne ni bhraonain ojoibi may 17 1961 je olorin omo ile ireland
saad al-abdullah al-salim al-sabah
kuwaiti
zainab balogun zainab balogun tí a bí ní ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹwàá ọdún 1989 jẹ́ òṣeré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni ìpínlè nàìjíríà ó bẹ́ẹ́rẹ̀ sì ni ṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni ìgbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún ó wá nínú àwọn tí òlùdásílè the j-ist tv ní ibi tí wọ́n ti má sọ̀rọ̀ nípa àṣà ilẹ̀ áfríkà àti àwọn ọ̀rọ̀ tí ó jọ mọ ó...
kùwéítì
ewébẹ̀ ewébẹ̀ ni àwọn ewéko tí ènìyàn tàbí ẹranko mìíràn máa ń jẹ gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ ènìyàn lè se ewébẹ̀ jẹ tàbí kí wọ́n jẹ ẹ́ ní tútù àǹfààní pọ̀ jáǹtirẹrẹ nípa jíjẹ ewébẹ̀ pàápàá jù lọ nínú àgọ́-ara ènìyàn púpọ̀ nínú àwọn ewébẹ̀ ló kún fún àwọn èròjà aṣaralóore bíi èròjà-ara afúnnilókun carbohydrate èròjà-ara amúnidàgbà...
saad al-salim al-sabah sheikh saad al-abdullah al-salim al-sabah kcmg hon lárúbáwá ‎ saʿd al-ʿabd allāh as-sālim as-sabāh 1930 13 may 2008 ló jẹ́ ẹ́mírì ilẹ̀ kùwéìtì àti aláṣe ológun ilẹ̀ kùwéìtì fún ìgbà ṣókí ọjọ́ mẹ́sàn láti 15 dé 24 january 2006 nígbà tó rọ́pò sheikh jaber sheikh saad jẹ́ ọ̀gá aláṣe ní ilé-iṣẹ́ ológ...
manning marable william manning marable may 13 1950 april 1 2011 ọ̀mọ̀wé ará amẹ́ríkà marable jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ètò ìgboro ìtàn àti àwọn ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ áfríkà amẹ́ríkà ní yunifásítì kòlúmbíà marable ló jẹ́ ọlùdásílẹ̀ àti olùdarí ilé-ẹ̀kọ́ fún ìwadìí nínú àwọn ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ áfríkà amẹ́ríkà ó kọ ìwé tó pọ̀ ó sì kópa nínú a...
yunifásítì ìlú ebute harcourt
akọ ẹlẹ́dẹ̀
rhinoceros
àgbánréré àgbánréré ni ìkan nñú irú-ẹ̀dá márùún oníka-tóṣẹ́kù ẹlẹ́sẹ̀ pátákó tó wà láyé nínú ìdílé irúẹ̀dá-àgbánréré rhinocerotidae àti àwọn irú-ẹ̀dá yìówù tó jọ wọ́n sùgbọ́n tí wọn kò sí láyé mọ́ méjì nínú àwọn irú-èdà tó wà láyé wà ní áfríkà mẹ́ta sì wà ní apágúúsù asia
zain asher zain ejiofor asher bíi ni ọjọ́ kẹtàdínlógbon oṣù kẹjọ ọdún 1983 jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà àti britain ó jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fún cnn international ni ilẹ̀ new york city ó darapọ̀ mọ́ ilé iṣẹ́ cnn ni odun 2013 ó tún má ṣise fún money magazine ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọn bíi ni balham london borou...
pearlena igbokwe pearlena igbokwe ni olórí ni universal television èyí tí ó jé ẹ̀yà kan lára nbc universal television group òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó wá láti áfríkà tí ó má se olórí fún ilé iṣẹ́ telefisionu ni orile-ede united states of america ó jẹ́ ọmọ ẹ̀yà igbo ni nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọn b...
maduka joana
jamestown virginia ibi ìtẹ̀dó jamestown ní ibi-àmúsìn ilẹ̀ virginia ló jẹ́ ibùgbé ibi ìtẹ̀dó àwọn gẹ̀ẹ́sì àkọ́kọ́ ní orílẹ̀ amẹ́ríkà
george lucas george walton lucas jr bọjọ́ìbí may 14 1944 ni aṣefílmù ọlọ́rẹ àoti oníṣòwò ará amẹ́ríkà lucas gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bíi ẹni tó ṣe àwọn fílmù bíi star wars àti indiana jones àti olùdásílẹ̀ àwọn ilẹ́-iṣẹ́ lucasfilm lucasarts 'àti industrial light magic òhun ni alága lucasfilm tẹ́lẹ̀ kí ó tó tàá fún the walt disne...
raphael saadiq raphael saadiq orúkọ àbísọ charles ray wiggins may 14 1966 ni akọrin akọ̀wé-orin onílù-orin àti olóòtú àwo-orin ará amẹ́ríkà ó gbajúmọ̀ bíi ọ̀kan nínú ọmọ ẹgbẹ́ olọ́rin tony toni toné ó ti ṣe olóòtú orin fún àwọn akọrin míràn bíi joss stone d'angelo tlc en vogue kelis mary j blige ledisi whitney houston ...
àgbájọ àwọn orílẹ̀-èdè aṣòkan
àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan ilẹ̀ amẹ́ríkà
sandra ezekwesili nigerian journalist sandra sopuluchukwu ezekwesili jẹ oniroyin àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni ilẹ̀ nàìjíríà òun ni atọkun fún eto ìròyìn drive time ati ètò hard facts lóri nigeria info 993 fm ni ìpínlè èkó ni nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé ètò-ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ rẹ̀ wọ́n bí sì ìpínlè port harcourt ni nàìjíríà òun nik...
yvonne ekwere yvonne imoh-abasi glory ekwere bíi ni ọjọ́ kẹta oṣù kẹta ọdún 1987 tí orúkọ inagi rẹ jẹ yvone vixen ekwere je agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati òṣèré òun sì ni atọkun ètò ẹ-weekly lórí silver bird television ó ti ṣe atọkun ètò lórí rythm 937 fm náà ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ vixen jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ akwa ibom ni ...
madagáskàr
àmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ madagáskàr
àsìá ilẹ̀ madagáskàr
ìtàn ilẹ̀ madagáskàr
tobechi nneji tobechi lawrence nneji bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kìíní ọdún 1987 tí orúkọ inagi rẹ jẹ tobe da diva jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati atọkun ètò lórí telefisionu ní ọdún 2013 thisday ni pé ètò rẹ ni àwọn gbọ́ ju ni ọ́sán ni apa ìlà-oòrùn ni orile-ede nàìjíríà ní ọdún 2013 ó gbajúmọ̀ fún àwọn ètò bíi top ten most...
nnenna egwuekwe nnenna egwuekwe bíi ni ọjọ́ kẹji lélógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1992 tí orúkọ inagi rẹ jẹ nenny b je ọmọ nàìjíríà ó sì jẹ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fún mtv base africa ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí nnenna sì ìpínlè èkó ó jẹ́ omo ìpínlè imo ni naijiria ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ aloysius primary school ni abuja fú...
moet abebe laura monyeazo abebe bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógbọ̀n oṣù keje ọdún 1989 tí orúkọ inagi rẹ jẹ moet abebe jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati òṣèré ni nàìjíríà ó béèrè sì ni di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tí ó bẹ́ẹ̀rẹ̀ sì ni ṣíṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fún soundcity tv ó ń má ṣe atọkun fún eto one on one show body soul ati global countdown show...
ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù amẹ́ríkà
mary uduma mary uduma bíi ni ọjọ́ meedogbon oṣù karùn-ún ọdún 1952 jẹ́ olùdarí ni ẹ méjì fún nigeria internet registration association nira òun ni alága fún nigeria internet governance forum ẹ̀kọ́ udoma gboyè nínú ẹ̀kọ́ accounting lati ilé ẹ̀kọ́ gíga tí institute of management technology àti university of lagos iṣẹ́ ud...
itunu hotonu itunu hotonu bíi ni ọjọ́ kẹji dínlógún oṣù kìíní ọdún 1959 jẹ́ ọmọ ogun orí omi nàìjíríà àti ayàwòrán fún ikọ́lé ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn obìnrin tí ó má je ọmọ ogun orí omi ó sì wá láàrin àwọn ayàwòrán àkọ́kọ́ fún ẹgbẹ́ ológun orí omi ni nàìjíríà ní oṣù kejìlá ọdún 2012 ó di obìnrin àkọ́kọ́ ni áfríkà tí ó má...
margaret oguntala margaret oguntala tí orúkọ inagi rẹ jẹ erelu jẹ́ enginia àti olùdarí fún bamsat nigeria limited òun ti se igbá kejì adarí fún nigerian society of engineers nse olukede fún association of professional bodies of nigeria ó ti ṣe alága fún nigeria society of engineers ni ẹ̀yà tí ikeja iṣẹ́ ó gboyè gẹ́gẹ́ ...
lola masha lola masha jẹ́ adarí fún olx àti olórí òwò fún google ni nàìjíríà òun ni oludasile ilé iṣẹ́ babban gona farmers service limited ẹ̀kọ́ lola gboyè enginia láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí university of virginia ó gbà phd nínú ẹ̀kọ́ enginia láti ọwọ́ uc berkeley college of engineering iṣẹ́ masha ni olùdarí fún olx ni nàì...
aisha augie-kuta aisha augie-kuta ti a bi ni ọjọ kẹrinla oṣu kẹrin ọdun 1980 jẹ oluyaworan ati oṣere fiimu ti orilẹ-ede naijiria ti o da ni ilu abuja arabinrin naa ni hausa lati ijoba ibile argungu ni ariwa nigeria o gba ẹbun naa fun oluṣọọda ẹlẹda ti ọdun ni ọdun 2011 the future awards augie-kuta ni onimọnran pataki t...
new edition new edition ni ẹgbẹ́ olórin rb ará amẹ́ríkà láti àdúgbò roxbury ní boston massachusetts tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 1978 wọ́n gbajúmọ̀ gan ní ìgbà àwọn ọdún 1980 àwọn ọmọ ẹgbẹ́ àkọ́kọ́ láti ìbẹ̀rẹ̀ ni ricky bell michael bivins ronnie devoe bobby brown àti ralph tresvant johnny gill dara pọ̀ mọ́ wọn lọ́jọ́ wájú...
boston massachusetts
ralph tresvant ralph edward tresvant ọjọìbí may 16 1968 ni akọrin akọ̀wé-orin òṣeré àti olóòtú àwo-orin ará amẹ́ríkà tó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́bí ìkan nínú ọmọ ẹgbẹ́ olórin rb new edition as a solo artist tresvant released the album ralph tresvant 1990
kwame ture kwame ture orúkọ àbísọ stokely standiford churchill carmichael june 29 1941 november 15 1998 jẹ́ alákitiyan ará trínídàd tò kópa nínú ìrìnkankan àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú ní orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà àti nínú pan-african movement|ìrìnkankan ìṣe pan-áfríkà lágbàáyé wọ́n bíi ní orílẹ̀-èdè trinidad sùgbọ́n ó dàgbà ní amẹ́rík...
stokely carmichael
howard university
yunifásítì howard yunifásítì howard ní èdè gẹ̀ẹ́sì howard university tàbí howard tàbí hu ni yunifásítì aládáni tó ní ìwé áṣẹ látọwọ́ ìjọba àpapọ̀ tó bùdó sí washington dc ní amẹ́ríkà yunifásítì howard jẹ́ ìkan nínú àwọn yunifásítì tí wọ́n dásílẹ̀ fún àwọn aláwọ̀dúdú hbcu ní orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà wọ́n dá yunifásítì howard...
jimi agbaje
sars-cov-2 ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa kòkòrò èràn náà fún ìjálẹ̀ àrùn 2019-2020 ẹ wo àjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019-2020 fún àrùn tó ún fà ẹ wo covid-19 kòkòrò èràn àrọ́lù àìsàn ìmín olóró gbígboró èrànkòrónà irú 2 tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ sáyẹ́nsì rẹ̀ sars-cov-2 severe acute respiratory syndrome coronavirus ...
ṣẹ́gun agbájé olúṣẹ́gun agbájé tí wọ́n bí ní ọdún 1964 jẹ́ alákòóso àti olùdarí ilé ìfowó-pamọ́ guaranty trust bank ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà<ref name=mr segun agbaje - managing director/ceo></ref> ó tún jẹ́ adarí fún ìgbìmọ̀ mastercard advisory board ti àrin gbùngbùn ilà oòrùn ilẹ̀ adúláwọ̀
who
àìsàn ìmúsára àìpé ìgbóguntàrùn
cyril ramaphosa matamela cyril ramaphosa ọjọ́ìbí 17 november 1952 ni olòṣèlú ará gúúsù áfríkà àti politician and the fifth and current ààrẹ ilẹ̀ gúúsù áfríkà 5k tó wà níbẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́