raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
george oguntade george adesola oguntade cfr con a bi ni ojo kewa osu keta odun 1940 je adajo agba ti o ti feyinti ni ilé-ẹjọ́ gígajùlọ ilẹ̀ nàìjíríà supreme court of nigeria laarin may 19 2004 si may 10 2010 |
sonya spence sonya spence jẹ́ akọrin olórin ìfẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè jamaica lára àwọn orin tí ó kọ tí ó lókìkí ni jet plane in the dark àti let love flow on |
adesola kazeem adeduntan adesola kazeem adeduntan a bi ni may 7 1969 jé omo orílé èdè nàìjíríà osise ile ifowopamo o tun je olusakoso ati oludari ile ifowopamo first bank of nigeria limited ati gbogbo ẹka re o bo ipo yi lati ipo ti o wa tele gege bi group chief financial officer and an executive director with the bank ... |
kemi adeosun kemi adeosun a bi ni 9 march 1967 jẹ́ ọmọ orílẹ́ èdè nàìjíríà ó si tún je minisita fun eto isuna orile-ede nàìjíríà lati ojo kokanla osu kokanla odun 2015 igbesi-aye re abi kemi adeosun si idile ogbeni adeosun ni odun 1967 si ilu london ti awon obi re je omo-bibi ipinle ogun ni orile ede naijiria o kekoo g... |
tayo aderinokun olutayo aderinokun may 8 1955 june 14 2011 jé omo orílé èdè nàìjíríà onísòwò ti o si tun je oludari ile ifowopamo guaranty trust bank titi di ojo ti o fi aye sile o si je okan lara awon ti o ti gba ami eye idalola member of the federal republic okan lara ami eye ti ijoba orile ede nàìjíríà ma n fi da aw... |
bola akindele adebola ismail akindele tí a bí ní oṣù kọkànlá ọjọ́ karùn-dín-lọ́gbọ̀n ọdún 1963 ní ibadan ìlú ọ̀yọ́ jẹ́ òǹtajà onímọ̀ràn ìṣòwò àti onínúure ó jẹ́ olùdárí alákoso ẹgbẹ́ ti courteville business solutions olùpèsè ti ìmọ̀-ẹ̀rọ àlàyé àti àwọn iṣẹ́ ìjáde ìlànà ìṣòwò ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ti ìgbìmọ̀ àwọn alámọ̀ràn ti... |
sarah alade sarah alade jé omo orílé èdè nàìjíríà ti o je adele gomina central bank of nigeria ni asiko ti lamido sanusi wa ni idaduro ki saa re o to pari olori orile-ede nàìjíríà nigba naa president goodluck jonathan ni o yan ni 20 february 2014 a yan alade gege bi adele gomina central bank of nigeria lati 20 february... |
ibukun awosika nigerian business magnate ibukunoluwa abiodun awosika tí wọ́n bí ní bilkisu abiodun motunrayo omobolanle adekola ní 24 oṣù kọkànlá 1962 jẹ́ obìnrin oníṣòwò nàìjíríà abáni-sọ̀rọ̀-ìyànjú àti òǹkọ̀wé ó jẹ alága tẹ́lẹ̀rí first bank of nigeria ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí-ayé àti ẹ̀kọ́ wọ́n bí i gẹ́gẹ́ bí i ọmọ kẹta nínú ọ... |
ilẹ̀ọbalúayé brítánì |
ilẹ̀ọbalúayé málì |
ilẹ̀ọbalúayé ghánà |
arise o compatriots |
agbègbè olúìlú ìjọba àpapọ̀ abùjá |
abùjá |
ìpínlẹ̀ kwárà |
kamẹrúùn |
bòkó àráámùù |
ìpínlẹ̀ kúárà |
abdusamet yigit abdusamet yigit gan abdussamet yigit a bi ni 1978 ni cizre ni a kurdish onkqwe ngbe ni norway o si a bi ni abule xirabê sosina ekun nisebin ni ariwa kurdistan o si iwadi itan ati imoye ati ti kọ ọpọlọpọ awọn iwe nipa awọn kurdish eniyan epics ni kurdish dialect kurmanji yigit akọkọ iwe faqi tayran ni a ... |
k1 de ultimate wọ́n bí ọlásúnkànmí wasiu àyìndé adéwálé marshal tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí k1 de ultimate ní ọjọ́ kẹta oṣ̀u kẹta ọdún 1957 march 3 1957 ní ìjẹ̀bú òde ìpínlẹ̀ ògùn ó jẹ́ olórin fújì ọmọ nàìjíríà ó di gbajú-gbajà olórin nípa bí ó ṣe fi àwọn ohun ìlù ìgbàlódé bíi ḱibọọdù sasofóònù àti jìtá kún orin fújì ìbẹ̀r... |
fidio ere a fidio ere jẹ ẹya ẹrọ itanna game ti o je ibaraenisepo pẹlu a ni wiwo olumulo lati se ina visual esi lori a fidio ẹrọ bi a tv iboju tabi kọmputa atẹle awọn ọrọ fidio ninu fidio ere asa tọka si a raster àpapọ ẹrọ sugbon bi ti awọn 2000 o tumo si eyikeyi iru ti àpapọ ẹrọ ti o le gbe awọn meji- tabi mẹta-onisẹp... |
donkey kong donkey kong jẹ ẹya olobiri game tu nipa nintendo ni 1981 o ti wa ni ohun kutukutu apẹẹrẹ ti awọn syeed game oriṣi bi awọn imuṣere fojusi lori maneuvering awọn ifilelẹ ti awọn ti ohun kikọ silẹ kọja kan lẹsẹsẹ ti awọn iru ẹrọ nigba ti sa fo lori idiwo ni awọn ere mario akọkọ ti a npè ni ogbeni video ati ki o... |
yunifásítì ìlú versailles yunifásítì ìlú versailles tabi yunifasiti versailles jẹ́ yunifásítì kan ní ìlú versailles fránsì uvsq ti wa ni àìyẹsẹ ni ipo ninu awọn ti o dara ju egbelegbe ni aye o ti wa ni paapa ogbontarigi imọ ti climatology ati atomosphere |
uvsq |
halle saale halle saale sẹyìn halle an der saale yi tumo si halle sunmọ awọn saale tabi halle/saale jẹ ilu kan ni jẹ́mánì awọn ilu ti wa ni be ni saxony-anhalt |
ewa demarczyk ewa maria demarczyk ojo ibi january 16 1941 kraków - 14082020 je olorin omo ile pólàndì |
akojọ ti awọn japan okeere footballers eleyi ni akojọ kan ti japan okeere footballers - japanese sepo bọọlu awọn ẹrọ orin ti o ti dun fun awọn japan orilẹ-bọọlu egbe bi o ti gbasilẹ nipasẹ awọn japan football association awọn akoonu 1 players 2 wo tun 3 jo 4 ita ìjápọ players imudojuiwọn november 14 2012 player ere ete... |
dättlikon colspan=2 align=center | colspan=2 align=center | dättlikon jẹ́ abúlé kan ní ìlài gúsu ilẹ̀ swísálandì ni ó n jẹ́ dättlikon |
aw restaurants a w restaurants jẹ akojọpọ awọn ounjẹ ounjẹ ounjẹ ounjẹ ti o ṣe iyatọ nipasẹ awọn ẹọti ati awọn ọti oyinbo a w jẹ gangan ile-iṣowo franchise akọkọ awọn franchises bẹrẹ ni california ni ayika 1921 a gba idanimọ ile lati awọn awọn ti awọn alabaṣepọ roy w allen ati frank wright awọn akojọ aṣayan ti ounjẹ ou... |
burger king burger king jẹ ajọ igbimọ ti ilẹ okeere ti o ta ikọju akọkọ iṣowo rẹ 1954 miami florida ọkan ninu gbogbo ile-iṣẹ burger ti awọn ile-iṣẹ ayanfẹ ọba ni hamburger ti a npe ni whopper nigbati burger ọba pinnu lati gbe iṣẹ wọn soke ni australia wọn mọ pe awọn oniṣowo kan ti iṣowo ile-iṣowo ti jẹ iṣowo-owo wọn ni... |
pizza hut pizza ahere èdè gẹ̀ẹ́sì pizza hut ti àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan amẹ́ríkà yara ounje ounjẹ ati ki o ni ẹka ni opolopo orile-ede ti wa ni almo onje ounje amoye pizza gbogbo iru sugbon o jẹ okhrykma o nfun awọn isopọ si ita iṣẹ awọn ohun elo ni afikun si awọn seese ti njẹ ni a ounjẹ |
carl's jr jr carl jẹ asayan ti ounjẹ ounjẹ ni west coast ti àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan amẹ́ríkà o bere pẹlu carl karcher ati ki o ti wa ni ini nipasẹ cke onje |
ernest sonekan |
ernest sonekan |
láyal abbùd layal abboud lárúbáwá a bi 15 may 1982 jẹ olugbala lebanoni olutẹrin orin music akọrin orin-orin oṣere orin dada awoṣe ẹsin musulumi ati oṣowo-owo |
oṣù kẹ̀sán 20 |
jeremiah timbut useni |
jeremíàh useni |
oluwarotimi odunayo akeredolu oluwarotimi odunayo akeredolu san or rotimi akeredolu ọjọ́ ìbí 21 july 1956 - 27 december 2023 jẹ́ olóṣèlú àti agbẹjọ́rò ará nigeria tó jẹ́ gómìnà ìpínlẹ ondo ní orílẹ̀ edè nàijíríà lọ́wọ́lọ́wọ̣́ akeredolu tún jẹ́ ìkan nínú àwọn agbẹjọ́rò àgbà ti ilẹ̀ nàìjíríà san tí ó sì jẹ́ ààrẹ ẹgbẹ́ am... |
yemi osinbajo olúyẹmí olúlékè òṣínbàjò tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù karùn-ún ọdún 1947 jẹ́ òṣèlú àti igbákejì ààrẹ orílẹ̀-èdè nàìjíríà láti ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù kàrún ọdún 2015 sí 2023 ó gorí àléfà fún sáà àkọ́kọ́ pẹ̀lú ààrẹ muhammadu buhari lọ́jọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2015 lọ́dún 2019 ó tún wọlé lẹ́ẹ̀k... |
oluyemi oluleke osinbajo |
aṣdodu aṣdodu jẹ ìlú kan ni israeli lori etikun mẹditarenia o ni orilẹ-ede ile tobi ibudo |
dick gregory richard claxton gregory ọjọ́ kejìlá oṣù kẹwá ọdún 1932 ọjọ́ ọ̀kàndínlógún oṣù kẹjọ ọdún 2017 jẹ́ aláwàdà alákitiyan eto araalu alárìíwísí olùkòwé oníṣòwò àti òṣèré ará áfíríkà bi amẹ́ríkà |
hardee's hardee's jẹ amerika ounje ti ko ni iye owo ti o bẹrẹ ni 1960 o jẹ opo ni awọn ilu midwestern ti amẹrika awọn ile tita ta awọn ege adie frites ati awọn hamburgers wilbur hardee ni oludasile ti hardee's |
kazuo ishiguro kazuo ishiguro ọjọ́ oṣù kọkànlá 1954 jẹ́ olùkọ̀wé tó gba ẹ̀bùn nobel nínú lítíréṣọ̀ ní ọdún 2017 |
lester speight lester speight ojoibi oṣù august 28 1963 je osere ara amerika |
ralphie may ralph duren ralphie may ojoibi oṣù february 17 1972 je osere ara amerika |
andy kaufman andrew geoffrey andy kaufman ojoibi oṣù january 17 1949 je osere ara amerika |
christina ricci christina ricci ojoibi oṣù february 12 1980 je osere ara amerika |
cam clarke cameron arthur cam clarke november 6 1957 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà |
moira kelly moira kelly ojoibi march 6 1968 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà |
donald trump donald john trump tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹfà ọdún 1946 ni ààrẹ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ẹlẹ́ẹ̀karùndínláàdọ́ta lọ́wọ́lọ́wọ́ 45k ó gorí àléfà ní ogúnjọ́ oṣù kìíní ọdún 2017 trump jẹ́ gbajúgbajà oníṣòwò kí ó tó dara pọ̀ mọ́ òṣèlú |
james comey james brien comey jr december 14 1960 jẹ́ agbejoro ará amẹ́ríkà to sise tele bi oludari federal bureau of investigation ile amerika |
anna netrebko anna netrebko ojoibi 18 september 1971 krasnodar ìsọ̀kan sófìẹ̀tì je olorin omo ile russia |
will smith |
will smith willard carroll will smith jr ojoibi september 25 1968 je osere olootu rapper alawada ati ako-orin ara amerika ni osu april 2007 newsweek pe ni osere to lagbarajulo ni hollywood smith ti je yiyan fun ebun golden globe marun ati ebun akademi meji be sini o ti gba ebun grammy merin |
stan wawrinka |
michael sata michael chilufya sata 6 july 1937 28 october 2014 je oloselu ara ile zambia to je aare ile zambia ikarun lati 23 september 2011 titi to fi ku ni 28 october 2014 oloselu awujo ni o lewaju egbe oselu patriotic front pf ni zambia labe aare frederick chiluba sata je alakoso eto ni ewadun 1990 gegebi ikan lara ... |
jerzy stuhr jerzy oskar stuhr ojoibi 18 april 1947 je osere ara polandi |
gabrielle union gabrielle monique union-wade born october 29 1972 je osere are amerika |
tracee ellis ross tracee ellis ross oruko abiso tracee joy silberstein october 29 1972 je osere ologe alawada ati olootu eto telifisan to gbajumo fun ere re bi dr rainbow johnson lori ere awada ile-ise telifisan abc black-ish tracee ellis ross je ikan ninu awon omo diana ross |
spanish language |
nikki giovanni yolande cornelia nikki giovanni jr ibi june 7 1943 je ako-ewi olukowe alawiso alakitiyan ati oluko ara amerika ikan ninu awon akoewi to gbajumojulo lagbaye ninu awon ise re ni awon iwe ewi awo-orin ewi ati awon ayoka orisirisi ti won da lori eya oro awujo ati iwe omode o ti gba opolopo ebun ninu won ni e... |
sean combs sean john combs ojoibi november 4 1969 to tun gbajumo pelu awon oruko itage re puff daddy puffy p diddy ati diddy je olorin rap akorin akowe-orin osere akotun awo-orin ati onisowo ara amerika won bi ni harlem o si dagba ni mount vernon new york o sise bi oludari talenti ni uptown records ko to da ile-ise ti ... |
puff daddy |
p diddy |
ipinle penssylvania |
ìgbà òṣèlú àkọ́kọ́ ilẹ̀ nàìjíríà |
àwọn ìpínlẹ̀ aṣọ̀kan amẹ́ríkà |
tukur yusuf buratai tukur yusuf buratai ojoibi 24 osu kokanla 1960 je igbakeji ogagun ara naijiria ati oga awon omose agbogun ile naijiria lowo ipo ti aare muhammadu buhari yan si ni osu keje 2015 o gba ipo ologun ni 1983 latigba na o ti sise ni ipo orisirisi bi oga alamojuto ati olukoni |
joseph akahan joseph akahan 12 april 1937 - may 1968 jẹ́ ọ̀gá ológun ti orílẹ̀ èdè nàìjíríà láti oṣù karún ọdún 1967 sí karún ọdún 1967 tí ó sì kú látàrí ìjàmbá ọkọ̀ òfúrufú tí ó wáyé nígbà ogun abẹ́lé nàìjíríà |
theophilus danjuma theophilus yakubu danjuma gcon fss psc ojoibi 9 december 1938 je ogagun to ti feyinti oloselu ati onisowo ara naijiria lati eya jukun o je oga omose agbogun naijiria lati july 1975 de october 1979 o si tun je alakoso oro abo labe ijoba olusegun obasanjo danjuma ni alaga ile-ise south atlantic petrole... |
aliyu mohammed gusau aliyu mohammed gusau ojoibi may 18 1943 oga agbogun ara naijiria to ti feyinti o ti je alakoso oro abo onimoran oro abo orile-ede fun aare naijiria otooto meji oga awon omose agbogun o se olori fun orisirisi ile-ise otelemuye besini o tun se oga alase nigerian defence academy |
luka yusuf luka nyeh yusuf |
abdulrahman bello dambazau abdulrahman bello dambazau ojoibi march 14 1954 jé ológun pèlú okùn ògágun onígbákejì tó tí feyintì láti agbogun ará naìjíríà àti lówólówó alákòso ètò abélé naìjíríà dambazau síse bí ògá omosé agbógun naìjíríà coas láàrín 2008 àtí 2010 nígbà tó gbéyìn ògágun ònígbákejì luka yusuf |
azubuike ihejirika azubuike ihejirika cfr ojoibi february 13 1956 je igbakeji ogagun agbogun ara naijiria to ti feyinti ati oga awon omose agbogun tele |
kenneth minimah |
chief of army staff nigeria |
ọ̀gá àwọn ọmọṣẹ́ agbógun nàìjíríà ọ̀gá àwọn ọmọṣẹ́ agbógun tàbí ọ̀gá ọmọṣẹ́ agbógun lásán chief of army staff ní èdè gẹ̀ẹ́sì ni ipò tó gajùlọ òsìṣẹ́ ológun ní ibiṣẹ́ agbógun ará nàìjíríà the position is often occupied by the most senior commissioned officer appointed by the commander-in-chief of the armed forces of nig... |
ella baker ella josephine baker december 13 1903 december 13 1986 je alawodudu ara amerika to je alakitiyan eto araalu ati eto omoniyan ti a bi ni ipinle virginia sugbon to dagba ni ipinle north carolina to si pari eko giga re nibe o sise ni opo gbogbo ile-aye re ni ilu new york o fibe sise leyin ago nibi to ti n se al... |
luis guillermo solís orúkọ yìí lo àṣà ìṣorúkọ ní èdè spéìn àkọ́kọ́ tàbí orúkọ ìdílé bàbá ni solís èkejì tàbí orúkọ ìdílé ìyà ni rivera luis guillermo solís rivera ojoibi 25 april 1958 je oloselu ara kosta rika to je lowolowo aare ile kosta rika lati 2014 |
andrew holness andrew michael holness on mp born 22 july 1972 je oloselu ara jamaika to je lowolowo alakoso agba ile jamaika lati 3 march 2016 leyin idiboyan gbogbogboo 25 february 2016 |
giannis adetokunbo giannis hugo adétòkunbọ̀ tàbí antetokounmpo gíríkì ọjọ́-ìbí k-6 oṣù kejìlá ọdún 1994 jẹ ọmọ yorùbá agba bọ̃lù-alápẹ̀rẹ̀ ara ilẹ̀ girisi adétòkunbọ̀ ungba bọ̃lù-alápẹ̀rẹ̀ fún milwaukee bucks ní nba ní orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà |
giannis antetokounmpo |
cicely tyson cicely louise tyson ojoibi december 19 1924 je osere filmu ati ori-itage ara amerika |
frances cress welsing frances cress welsing oruko abiso frances luella cress march 18 1935 january 2 2016 je oniwosan okan ara amerika aroko re to ko ni odun 1970 the cress theory of color-confrontation and racism white supremacy je iwe to se pataki nipa itumo iwa iseojusaju awon oyinbo |
rosie stephenson-goodknight rosie stephenson-goodknight tí a tún mọ̀ sí rosiestep ní wikipedia jẹ́ olótú wikipedia ọmọ ìlú amẹ́ríkà tí ó gbìyànjú láti ri wípé ojú opó ìmọ̀ ọ̀fẹ́ yìí jẹ́ oun tí takọ tabo á má a dásí tí ó sì ṣe àgbékalẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ètò tí ó jẹ́ ki iye àwọn àyọkà nípa obìrín tó póṣùwọn pọ̀ síi ó ti kọ ọ̀p... |
iyari afamdi afamdi oruko iyari ile nijer ati naijiria iyari afamdi fe agbara ati ogun awo omo ati duro jaye afam ahmadi amara emecca halimnye isa mmadu nnadi nnamdi nnenadi onwa ruquayat oruko awon omo iyari afamdi |
gil scott-heron gilbert gil scott-heron april 1 1949 may 27 2011 je olorin soul ati elewi jazz ati olukowe to gbajumo agaga fun ise re bi onidan oro siso |
gil scott heron |
simon shelton simon shelton bíi ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kínín ọduń 1966 jẹ́ òṣèré gẹ̀ẹ́sì |
nikky smedley nicola jane nikky smedley bíi october 1970 jẹ́ òṣèré gẹ̀ẹ́sì |
pui fan lee pui fan lee bíi july 1971 jẹ́ òṣèré gẹ̀ẹ́sì |
chidinma chidinma ekile ojoibi 2 may 1991 tò gbájùmọ̀ pẹ́lù òrùkọ̀ òrì-ìtágé rẹ́ ńì chidinma jẹ́ akọ̀rìń átì òlòrìń àrá ìlẹ́ naijiria ńì ọ̀dùń 2010 ńì íràwọ̀ rẹ́ kòkò yò ńìgbá tò gbá ìpò kìńì lòrì étò tèlìfìṣáń tò ń jẹ́ project fame west afrìká íbẹ́rẹ ayé rẹ̀ chidinma ekile wọ̀ń bì ńì ádùgbò kétù ńì kòṣọ̀fẹ́ ńì ìpìńlẹ́... |
chidinma ekile |
viktor suhorukov viktor suhorukov oṣù kọkànlá ọjọ́ kẹwá 1951 jẹ́ òṣèré ará russia ó ti kópa nínú fíìmù àti amóùn-máwòran bíi àádọ́ta láti ọdún 1974 |
mùhammádù bùhárí |
jemes ibori |
ìdábẹ́ fún ọmọbìrin ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà ìdábẹ́ fún ọmọbìrin ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà jẹ́ àṣà tí wọ́n ti fòfin dè ààrẹ tẹ́lẹ̀ goodluck ebele jonathan buwọ́ lu òfin tí ó fòpin sí àṣà yí ní oṣù karún ọdún 2015 orílẹ̀ èdè nàìjíríà ni àṣà dídábẹ́ fún ọmọbìnrin tí wọ́pọ̀ jù ní gbogbo àgbáyé síbẹ̀síbẹ̀ ó ti ń dínkù ọ̀kànléló... |
àjọ tí ó ń mójú tó ońjẹ àti oògùn ti orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà àjọ tí ó ń mójú tó ońjẹ àti oògùn ti orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà tí a mọ̀ sí fda tàbí usfda jẹ́ ààjọ ìjọba àpapiọ̀ tí ìlera ti orílẹ̀ èdè àmẹ́ríkà |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.