raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
bodija bódìjà ni àdúgbò kan ní ìlú ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ àdúgbò yí di gbajú gbajà pẹ̀lú ilé ìgbé alákọ̀ọ́pọ̀ tí wọ́n kọ́ síbẹ̀ láàrín ìgboro ìlú ìbàdàn lẹ́yìn ìgbòmìnira ilẹ̀ nàìjíríà ní ọdún 1960 irúfẹ́ ilé ìgbé méjì ni ó wà ní àdúgbò náà àkọ́kọ́ ni bódìjà ayé àtijọ́ àti bódìjà tìgbàlódé bẹ́è sì ni ó tún jẹ́ ilé ìgb... |
àtòjọ àwọn ìwé ìròyìn olójoojúmọ́ ilẹ̀ ǹàijíríà àtòjọ àwọn ìwé ìròyìn olójoojúmọ́ ilẹ̀ ǹàijíríà àtòjọ yìí dá lórí àwọn ìròyìn abẹlé àti ti ok̀èrè tí wọ́n ń tẹ̀ jáde lójoojúmọ́ jákè jádò ilẹ̀ nàìjíríà àwọn ìwé 2 3 http//digitallibmsuedu/projects/africanjournals/ https//booksgooglecom/booksid=jj4j-axgdaqc https//booksgoo... |
adéyẹyè ẹnitàn ògúnwúsì ọ́ba adéyeyè enitàn ògúnwúsì jẹ́ ọba tó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni kábíyèsí tó wà lórí ìtẹ́ oòni ti ìlú ilé-ifẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ilẹ̀ yorùbá láti ọduń 2015 ni ó ti gorí ìtẹ́ àwon babańlá rẹ̀ ìgbásíayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ọba ògúnwùsì bẹ̀rẹ̀ ilé-ìwé alákọ̀óbẹ̀rẹ̀ ni ṣubúọ́lá memoria... |
ogbono soup ọbẹ̀ ọ̀gbọ̀nọ̀ yorùbá àpọ̀n efik melon jẹ́ ọbẹ̀ kan ní ilẹ̀ nàìjíríà tí wọ́n ń sè pẹ̀lú èso àpọ̀n gbị́́gbẹ the local name for irvingia seeds àti àwọn ǹ kan óṇ́jẹ ìbílẹ̀ mìíràn àpọ̀n lílọ̀ náà má ń fún ọbẹ̀ ní àwọ̀ dúdú yàtọ̀ sí kúrú àpọ̀n yìí wọ́n tún ma ń fi omi epo ata gígún ẹran àti àwọn ohun tó lè mú ọb... |
ọbẹ̀ ọ̀gbọ̀nọ̀ ọbẹ̀ ọ̀gbọ̀nọ̀ yorùbá àpọ̀n jẹ́ ọbẹ̀ kan ní ilẹ̀ nàìjíríà tí wọ́n ń sè pẹ̀lú èso àpọ̀n gbị́gbẹ the local name for irvingia seeds àti àwọn ǹ kan óṇ́jẹ ìbílẹ̀ mìíràn àpọ̀n lílọ̀ náà má ń fún ọbẹ̀ ní àwọ̀ dúdú yàtọ̀ sí kúrú àpọ̀n yìí wọ́n tún ma ń fi omi epo ata gígún ẹran àti àwọn ohun tó lè mú ọbẹ̀ dùn si... |
garfield |
disney |
lamidi adeyemi iii a bí aláàfin ọ̀yọ́ ọba làmídì ọláyíwọlá adéyẹmí iii ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kẹwàá 1938-2022 ó jẹ́ ọba tó wà lórí ìtẹ́ aláàfin lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ìlú ọ̀yọ́ |
ẹ̀rìn-ilé ẹ̀rìn-ilé jẹ́ ìlú kan ní apá àrin gbùngbùn gúsù ní ìpínlẹ̀ kwárà ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà mòjé college of education mòjé college of education ni ó jẹ́ ilé ẹ̀kọ́ tí ó ń kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ nímọ̀ ìkọ́ni tí ó je ti ìjọba ní ó kalẹ̀ sí ìlú ẹ̀rìn-ilé ilé ẹ̀kọ́ náà ni ó ń kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ ìkó́ni èdè ìmọ̀ ẹ... |
dele odule a bí délé òdúlé tí a bí lọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kọkànlá ọdún 1961 jẹ́ àgbà òṣèré tíátà àti olótùú-àgbà ní ọdún 2014 wọ́n yaǹ-án láti gba àmìn-ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèré yorùbá ni best of nollywood awards fún ipa tí ó kó nínú sinimá àgbéléwò kori koto òun ààrẹ àwọn òṣèré tíátà àti sinimí àgbéléwò ní ... |
délé òdúlé délé òdúlé ọjọkẹtàdínlógún oṣù kọkànlá ọdún 1961 jẹ́ àgbà òṣèré tíátà àti olótùú-àgbà ní ọdún 2014 wọ́n yaǹ-án láti gba àmìn-ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèré yorùbá ni best of nollywood awards fún ipa tí ó kó nínú sinimá àgbéléwò kori koto òun ààrẹ àwọn òṣèré tíátà àti sinimí àgbéléwò ní orílẹ̀-èdè nàìjí... |
kola tubosun kọ́lá túbọ̀sún jẹ́ akọ́mọlédè oǹkọ̀wé ọ̀mọ̀wé ati olùgbásàga ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí iṣẹ́ ipa rẹ̀ ti gbajúmọ̀ ní ọ̀pọ̀ ẹ̀ka èkọ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ lítírésọ̀ ìròyìn ati ẹ̀ka akọ́mọlédè o jẹ́ aṣojú àṣà ni southern illinois university edwardsville 2009 ó ti gba àkànṣe àmì-é̀yẹ premio ostana fuń litireṣọ̀ èdè abíni... |
basshunter basshunter jonas erik altberg ọjọ́ 22 oṣù kejìlá 1984 jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀-èdè swídìn |
jonas erik altberg |
ariyike akinbobola |
aríyìíkẹ́ akínbòbọ́lá a bí aríyìíkẹ́ lawal-akínbọ̀bọ́lá ní ọjọ́ kẹẹ̀édọ́gbòn oṣù kẹẹ̀rin ọdún 1982 o je olootu orisiirisii eto lori ero tẹlifịṣàn oníròyìn àheso agbẹjọ́rò àti òṣèré sinimá àgbáléwò since 2011 she has worked as an associate producer and tv presenter for spice tv a fashion and lifestyle channel on the dst... |
ìfẹ́ orílẹ́-èdè ẹni ìfẹ́ orílẹ́-èdè ẹni jẹ́ aáyan ìfọkànsìn láti fìfẹ́hàn fún orílẹ̀-èdè ẹni ní ìfọwọ́sọwọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ará ìlú tí ìṣẹ̀dá wọn jọra èyí lè jẹ́ àpapọ̀ orísìírísìí àdámọ́ tó jẹ mọ́ ìlú ẹni lára wọn ni ẹ̀yà àṣà ètò-òṣèlú tàbí ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ó jẹ́ àkójọpò ìmọ̀ tó sunmo ìgbórílẹ̀-èdè ẹni ga nationalism |
juliet ibrahim |
wizkid ayodeji ibrahim balogun ojoibi 16 july 1990 lori ere itage ama n pe ni wizkid o je̩ olukọrin ti owa lati ilu naijiria lati ọmọ ọdun mọkanla ni oti bẹrẹ sini kọrin otun ṣe record pẹlu awọn ọmọ ẹgbẹ glorious five ti ohun ati awọn ọrẹ rẹ dasilẹ ni ọdun 2009 arakunrin banky w gba wizkid si inu ẹgbẹ akọrin rẹ eyi tin... |
akinwunmi ambode akínwùnmí aḿbọ̀dé tí a bí ní ọ̣jọ́ kẹrìnlá oṣù kẹfà ọdún 1963 jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ gómìnà ìpínlẹ̀ èkó láàrin ọdún 2015 sí 2019 ó ti fìgbà kan jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba fún ọdún mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n ó jẹ́ olùgbaninímọ̀ràn lórí ìsúnná owó kí ó tó wá díje dupò gómìnà ní ìpínlẹ̀ è... |
fémi pedro olúfẹ́mi fémi pedro tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kìnínní ọdún 1955 ni ilu eko tí fìgbà kan jẹ́ igbákejì gómìnà ti ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà latí ọdún 2003 títí di ọdún 2007 kí a tó dìbò yàn án pẹ̀lú bọ́lá tinúbú ó jẹ́ ó̀gá àgbà ilé-iṣẹ́ àti ọ̀kan lára àwọn òlùdásílẹ̀ ilé-iṣé first atlantic b... |
pọ́nna ìkọ kederepọ́nna jẹ́ ọ̀rọ̀ tàbí gbólóhùn kan ṣoṣo tí ó ní ìtumọ̀ tó ju ẹyọ kan lọ ó jẹ́ ọ̀rọ̀ tí ìtumọ̀ rẹ̀ kò dá geere àbùdá kan gbòógì tí ọ̀rọ̀ tàbí gbólóhùn pọ́nna máa ń ní ni àì ní ìtumọ̀ kan pàtó ó jẹ́ ọ̀rọ̀ tàbí gbólóhùn tí ìtumọ̀ rẹ̀ kò dúró sójú kan bí àpeere ẹ̀wà èyí lè túnmọ sí ohun tí ó dára bákan náà... |
igbó olodùmarè igbó olódùmarè jẹ́ ìwé-ìtàn àròsọ méèrírí tí ọgb́eni daniel o fágúnwà ó jẹ́ ìwé-ìtà àròsọ àkọ́kọ́ tí a kọ lédè yorùbá àti ní ilẹ̀ adúláwò ̣áfíríkà a kọ ó ní ọdún 1949 òun sì ni ìwé-ìtàn àròsọ kejì òǹkọ̀wé náà daniel o fágúnwà |
akínsànyà sunny ajọ́sẹ̀ akínsànyà sunny ajọ́sẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí a bí ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kejì ọdún 1946 ó j̣́e olóṣ̀elú àti ògá-àgbà òṣìṣẹ́ ìjọba ó ti fìgbà kan jẹ́ olórí ilé-iṣé ìjọba fún àwon òṣìṣé ní ìpínlẹ̀ èkó láti oṣù keje ọdún 2004 sí oṣù kejì ọdun 2006 |
jagunjagun jagunjagun jẹ́ akọni tí ó máa ń jagun pàápàá jùlọ láàárín ẹ̀yà ìlú tàbí ẹbí kan láẁujọ yorùbá a máa ń ní ìran jagunjagun àwọn ni wọ́n sáàbà máa ń joyè ajagun tàbí balógun |
rainat komolafe rainat komolafe jẹ oludari ati oludasilẹ babiesessence o jẹ oludari ile-iṣẹ meji babiesessence ti o n koni nipa bi a ṣe n gbaradi fun ọmọ tuntun jojolo ati nikktun ile itaja ohun elo amaradan ati bẹ bẹ lọ rainat jẹ ẹni ti o mu eto gbigbaradi fun ọmọ tuntun jojolo ni okunkundu ati ṣiṣeowo babiesessence n... |
zainab ashadu zainab ashadu je oludasile ile ise zashadu ton se apo agbekowo lorisirisi to jasi pe awon ohun igbalode ni meremere bi kase nkan pelu awo omi ati lilo aworan asa aye awon babawa tohunti fifi owo hun awo eran taamo si leather ni ede geesi towa lati apa ariwa naijiria awon eyan nife si ise owo arabinrin yii... |
mary alimi mary bashua-alimi jẹ osiṣẹ continental broadcasting service ti wọn jẹ oludasilẹ tvc ati rc o pari ni ile-ẹko ifasiti ilu eko |
osula ebuwa patricia osula ebuwa patricia ti awọn eyan mọ gẹgẹbii uwatricia jẹ olukọ-orin ati olufuni ni ounjẹ ẹmi lati ilu ẹdọ |
zainab ashade |
john mccain |
all progressives congress all progressives congress apc kọ́ngrẹ́sì gbogbo àwọn onítẹ̀síwájú ni ede yoruba je egbe oloselu kan ni naijiria to je didasile ni ojo 6 osu keji odun 2013 lati kopa ninu idiboyan odun 2015 |
it |
àmàlà àmàlà jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn oúnjẹ tó gbajúmọ̀ nínú àwọn oúnjẹ ìran yorùbá lórílẹ̀-èdè nàìjíríà èlúbọ́ iṣu gbágùúdá tàbí ọ̀gẹ̀dẹ̀ ni wọ́n fi máa a ṣe àmàlà a o ti be̩fo̩ pelu sisa si orun is̩u tabi paki ti afe̩ lo fun elubo̩ àmàlà latara wipe is̩u ti a fe̩ lo fun elubo̩ ti gbe̩ ni àmàlà fi ni awo̩ duduàmàlà jẹ ounjẹ... |
erin-ijesha waterfalls erin-ìjẹ̀sà omi-ìṣàn orókè tí a tún mọ̀ sí omi-ìṣàn orókè olumirin wà ní erin-ìjẹ̀sà ó jẹ́ aṣòùnfà ìrìn-afẹ́ ní ìjọba-ìbílẹ̀ oríadè ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun nàìjíríà ìtàn sọ pé ọkàn lára àwọn ọmọ odùduwà ló ṣe àwárí omi - ìṣàn-orókè yìí ni 1140ad wàyí ooo gẹ́gẹ́bí the nation ṣe sọ àwọn ọdẹ ló ṣe àwárí omi ì... |
àlébù àlébù lè jẹ́ |
hermann melville |
keats |
amala |
mutiat mustapha/sandbox/2 tiwatope savage-balogun bii ni ọjọ karun oṣu keji ọdun 1980 ti awọn eniyan mọ si tiwa savage jẹ akọrin oluṣakoso orin oniṣẹ ati oṣere ilu naijiria lọwọlọwọ o ni iṣowo ṣiṣakoso-orin pẹlu sony/atv music publishing savage fi ọwọ si adehun iṣẹ pẹlu mavin records ni ọdun 2012 o tun fi ọwọ si adehun... |
tiwa savage tiwatope savage-balogun tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kejì ọdún 1980 tí àwọn ènìyàn mọ́ sí tiwa savage jẹ́ akọrin olùṣàkóso orin oníṣẹ́ àti òṣèré ìlú nàìjíríà ó fọwọ́ síwèé pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ òǹtẹ̀wé kan sony/atv music publishing savage fi ọwọ́ síwẹ̀ẹ́ iṣẹ́ pẹ̀lú mavin records ni ọdun 2012 ó tún fi ọwọ́ síwẹ̀ẹ́ ... |
oro orò wà nínú àwọn àjọ̀dún ńlà tí àwọn yorùbá ma ǹ ṣe ní ọdọọdún ọdún orò jẹ́ ọọ̀kan pàtàkì nínú ọdún tí àwọn ẹ̀yà yorùbá ma ń ṣe oro si je osa kekere kan ti a mo si olorun ogun ara igi agbon lati gbe oro jade osa nla gidi gan ni oro je won a si ma boo ni odoodun oro je osa kan to sepe omo okunrin nikan lo le foju ri... |
fela durotoye adetokunbo olufela oluwafeolami durotoye ti a bi ni ilu ibadan ipinle oyo ni ọjọ 12 may 1971 jẹ olugbamoran oniṣowo amoye alakoso ati agbọrọsọ agbara o jẹ aare ti gemstone nation builders foundation ti kii ṣe èrè eto ti kii ṣe ijọba ti o ni ifojusi si awọn ọdọ ikẹkọ si iyipada alakoso ati iyipada awujo fe... |
falz nigerian rapper folarin falana ti a bi ni oṣu kẹwa 27 ọdun 1990 ni ipinle eko ti a mọ julọ nipasẹ orukọ igbimọ rẹ falz jẹ olukọni ti nigeria olukopa ati akọrin o bẹrẹ iṣẹ rẹ lakoko ti o wa ni ile-iwe giga lẹhin ti o ti ṣe ẹgbẹ kan ti a pe ni awọn ọmọde ile-iwe pẹlu ọrẹ rẹ ṣaaju ki o to iṣẹ ọmọ-ọdọ gẹgẹbi akọrin or... |
fela durotoye |
jean pierre boyer |
auguste marie francois beernaert |
bari bari ni bari bäre titi 1931 bäre delle pugghjë jẹ ilu itali ti 322 018 olugbe olu-ilu puglia o jẹ ti italia mẹsan ti o wọpọ nipasẹ olugbe kẹta ti mezzogiorno lẹhin naples ati palermo ilẹ agbegbe rẹ jẹ kẹfa ti italy pẹlu fere 1 300 000 olugbe o tun mọ fun jije ilu ti awọn ibi ipamọ ti st nicholas isinmi ipo yii ti ... |
èdè ítálì itali jẹ ede ti a sọ ni italia nipa nipa awọn eniyan ti milionu mẹwa baba wa ni itali standàrd padre nostro che sei nei cielisia santificäto il tuo nomevenga il tuo regnosia fatta la tua volontà come in cielo così in terradacci oggi il nostro pane quotidianoe rimetti a noi i nostri debiticome noi li rimettiam... |
ede belarus ede belarus ni a sọ ni belarus ati pe a kọ sinu ahbidi cyrillić baba wa ni belarus ойча наш каторы ёсць у небе свяціся імя тваё ды прыйдзе царства тваё хай будзе воля твая як на небе так і на terra dacci дзень хлеб наш надзённы і даруй нам нашы debiticome мы даруем нашы даўжнікі і ня ўводзь нас у спакусу ал... |
naomi osaka láàrin orúkọ ará japan yìí orúkọ ìdílé ni osaka naomi osaka 大坂なおみ ōsaka naomi born 16 october 1997 jẹ́ agbá bọ́ọ̀ ẹlẹ́yin orí ọ̀dàn fún ilẹ̀ olómìnira japan òun ni agbá bọ́ọ̀lù ẹlẹ́yin orí ọ̀dàn ará japan àkọ́kọ́ tó gba ife-ẹ̀yẹ ìdíje grand slam nígbà tí ó borí alátakò rẹ̀ serena williams nínú àṣekágbá ìdíj... |
mandiraja mandiraja je ipile-agbegbe ni indonesia mandiraja je 300 km-õrùn ti jakarta |
simpson |
us |
atlanta blue atlanta blue jẹ́ orin ti don reid kọ sílẹ̀ tí ẹgbẹ́ the statler brothers kọ wọ́n ṣe àgbéjáde rẹ̀ ní ọdún 1984 gẹ́gẹ́ bíi orín àkọ́kọ́ tówà ní álúbọ́mù wọn tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ atlanta blue orin yìí wà ní ààyè kẹta ní àtẹ àwọn ẹyọ orín ìlú tí ógbónà ní us |
antlanta blue |
ovy's voice ovy's voice ohun ovy je fiimu ti a gbe jade ni odun 2017 ni orile-ede naijiria fiimu na je ere itage ti o da lori oro ife biodun stephen ni o ko itan naa ti o si gbe jade oludari fiimu naa ni dimeji ajibola fiimu naa so nipa asaraloso kan ti o ya odi ti o wa ni ife si omo onibara re kan o si tun fi idi re m... |
banana island ghost banana island ghost òkú erékùsù ọ̀gẹ̀dẹ̀ jẹ fiimu ti a gbe jáde ni ọdún 2017 olùkọ̀tàn àti oludari fiimu naa ni bb sasore olùdarí àgbà fiimu naa ni derin adeyọkunnu ati biọla alabi àwon òṣèré tí o kó'pa ninu fiimu naa ni ali nuhu saheed balogun tina mba àti bimbo manuel ìtẹ́wọ́gbà àjọ tí o ńṣe àgbéy... |
eko eko láì fi àmì si lè t́oka sí ìlú ìlú èkó ní oríléèdè nàìjírìà tí atún fi sọ orúko ìpínlẹ̀ rẹ̀ oúnjẹ oúnjẹ ẹ̀kọ lati inú àgbàdo ìmọ̀ ẹ̀kọ́ tí àń kọ́ láti kún fún ìmọ̀ |
búkan |
omolola itayemi omololá ìtáyemí jẹ́ akọ̀ròyìn àti àrẹ national association of travel and tourism writers of nigeria attwon arìnrìn àjò àti ìgbafẹ́ ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà |
anuli ola olaniyi anuli ola olaniyi je onise awujo oluko oro to n lo si ori ayelujara ati oludasile heir |
ijeoma balogun ijeoma balogun je onise iroyin nipa igbesi aye osi tun je oludasile ati alase ile ise redrick public relations ijeoma balogun je alara to logbon pelu opolopo iriri aye omu ka ko ise ribiribi lokunkundun fun ti eroungba ise laye pelu okan pataki lara imu idagbasoke ba eso fun eyan ni ile naijiria |
bolatito aderemi-ibitola bolatito aderemi-ibitola bii ni ọjọ kokanlelogun oṣu kini ọdun 1993 je omo bibi ilu eko naijiria o si lo si ilu amerika ni odun 2000 o si pada si naijiria ni odun 2014 bolatito gba iyi eko masters ninu eko ikopa ijinle ni tisch school of the performing arts yunifasiti new york o gba iyi eko bac... |
olayemi ogunwole ọláyẹmí ògúnwọlé jẹ́ gbajúgbajà pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ rẹ̀ honey pot lórí èrò àsọ̀rọ̀-mágbèsì àti èrọ amóhùn-máwòrán tvc communications ní ìpínlẹ̀ èkó ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ oníṣẹ́ honey pot kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú èdè gẹ̀ẹ́sì nílé ẹ̀kọ́ àgbà ilé ifẹ̀ ọbáfẹ́mi awólọ́wọ̀ university nàìjíríà iṣẹ́ rẹ̀ ìbẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìròyìn ... |
adenike akinsemolu adenike adebukola akinsemolu je olukoni nipa ayika naijiria ati onisowo awujo adenike je olukoni ni yunifasiti obafemi awolowo ile-iwe koleji adeyemi o je gbajumo nipa asiwaju onimo lori eto ayika adenike je oludasile green campus initiative ti o n se agbero fun ayika akoko iru re ni ogba ile-iwe gig... |
ainehi edoro ainehi edoro ni wọ́n bí ní december 11 ó jẹ́ ̀ònkọ̀wé ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà òun ni olùdásílẹ̀ àti olùgbéjáde ìwé brittle paper ó tụ́n jẹ́ igbá-kejì ọ̀jọ̀gbọ́n professor of global black literature ní ilé ẹ̀kọ́ àgbà university of wisconsin-madison ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ lásìkò tí ó ń kẹ́kọ̀ọ́ láti gboyè ìmọ̀ ìjìnlẹ... |
oreoluwa lesi oreoluwa lesi je̩ o̩kan pataki ninu onisowo to gbaju gbaja o̩mo̩ naijiria pe̩lu onise̩ aje to gba e̩ko lati ile o̩ba uk owun ni oludasile ati oludari ile ise̩ women's technology empowerment centre wtec aagbari olu ile ise̩ ti ki se fun eree a non-profit organisation eyi to n ro awo̩n obinrin pelu o̩mo̩de ... |
bolatito aderemi ibitola |
new money 2018 film new money owó tuntun jẹ́ fíìmù eré ìtàgé apanilẹrin tí a gbé jáde ní ọdún 2018 ni orile-ede nàìjíríà tọpẹ ọṣhin ni oludari ere náà nígbàtí ilé isẹ́ inkblot productions àti filmone gbé e jade fíìmù na só ìtàn ọmọbìnrin kan ti o n ba ni ta'jà ti o ni èròngbà láti di aránṣọ ti o wá ṣàdédé rí ìpín tirẹ̀... |
irú parkia filicoidea00jpg irú locust beans jẹ́ ọ̀kan nínú ìsebẹ̀ amọ́bẹ̀dùn iru jẹ èròjà ọbẹ̀ nílẹ̀ yorùbá àti káàkiri ibi tí wọ́n ti mọ ìwúlò rẹ̀ a máa ń fi irú sí ọbẹ̀ láti fi jẹ́ kí ó ní adùn àti òórùn dáadáa awọn ọbẹ ti a le fi irú si ni ọbẹ ila ọbẹ ewedu ọbẹ ẹfọ ọbẹ ata ọbẹ egusi ọbẹ ọgbọnọ ati bẹẹ bẹẹ lọ irú ni ... |
ọbẹ yọ ọbẹ yọ jẹ orukọ awọn ọbẹ to maa fa tikọ tabi yọ lọwọ bi apejuwe ọbẹ ila ọbẹ ewedu ọbẹ ọgbọnọ tabi eyi ti a nọ si apọn ọbẹ yọjẹ ọbẹ to wọpọ ni apa ariwa iwọ irun ati apa ariwa busu orun ni ilẹ naijiria irisi ọbẹ yi maa n ki yo si ma yọbọlọ ti a ba njẹ yala pẹlu ṣibi tabi pẹlu ọwọ wa awọn ounjẹ ti an fi jẹ ọbẹ yọ ... |
jack lalanne francois henri jack lalanne september 26 1914 january 23 2011 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà |
stefán karl stefánsson stefán karl stefánsson july 10 1975 august 21 2018 jẹ́ òṣèré ará íslándì |
hervé villechaize hervé jean-pierre villechaize april 23 1943 september 4 1993 je osere ara amerika |
magnús scheving magnús örn eyjólfsson scheving november 10 1964 jẹ́ òṣèré ará íslándì |
caroll spinney caroll edwin spinney tí a bí lọjọ́ merindinlogbon oṣù kejila ọdún 1933dágbére fáyé ní ọjọ́ kejo oṣù kejila ọdún 2019 december 26 1933- december 8 2019 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà |
édouard adolphe casimir joseph mortier |
guðmundur þór kárason guðmundur þór kárason june 14 1974 jẹ́ òṣèré ará íslándì |
marie françois sadi carnot |
new money tv series new money owó tuntun jẹ́ eré orí ẹ̀rọ mohùnmáwòrán ni ilu amẹ́ríkà tí o bọ́ s'órí afẹ́fẹ́ ni ọjọ́ kọkan-din-lọgbọn oṣu karun ọdun 2015 l'órí ẹ̀rọ ayélujára mohùnmáwòrán e eré yi ti a pín sí abala mẹ́fà dá l'órí bí àwọn tí ó l'ọ́rọ̀ púpọ̀púpọ̀ ṣe ma n na owo wọn àti iru igbe ayé ti wọn ma n gbe ilé i... |
addison timlin addison jayne timlin ojo ibi ojo kokan din logbon osu kefaodun 1991 je osere binrin omo ile amerika ti a mo si kami lerner ninu ere ilu ti ko fe ki oorun wo the town that dreaded sundown 2014 ati colleen lunsford ninu ere little sister omobirin kekere 2016 a mo fun ipa re gege bi sasha bingham ninu igba ... |
alhaji rájí àlàbí owónikókó alhaji muhammed rájí àlàbí owónikókó jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríàolórin àpàlà wọ́n bí rájí ní ìlú òró ní ijoba ibile irepodun ìpínlẹ̀ kwárà |
ebun oloyede olaiya alhaji lukman ẹ̀bùn olóyèdé ọláìyá tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí igwe jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà àti òṣèré sinimá àgbéléwò wọ́n bí ẹ̀bùn olóyèdé ní ilú kẹ́nta òkè-èjìgbò abẹ́òkúta ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ọláìyá lọ sí ilé ìwé alákọ̀ọ́bọẹ̀rẹ̀ stjudes ní ìlú abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ ògùn tí ó sì tún tè síwájú nínú ẹ̀kọ́ ... |
egbé akómolédè ẹgbẹ́ akọ́mọlédè àti àṣà yorùbá jẹ́ àgbárí-jọ-pọ àwọn olùkọ́ nílé ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ girama àti ilé ẹ̀kọ́ fásitì ti ìjọba pẹ̀lú aládàáni jákè jádò ilẹ̀ nàjíríà ẹgbẹ́ yìí ń ṣojú yorùbá níbi ìgbé lárugẹ èdè àṣà àti ìdàgbà sókè ìṣèṣe yorùbá |
babalola chinedum peace babalola chinedum peace née anyabuike fas faas wà nínú àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n ọmọ nàìjíríà tó jẹ́ inímọ̀ nípa egbò igi pharmacy tó tún jẹ́ obinrin àkọ́kọ́ elégbògi ìbílẹ̀ fásítì ìlú ìbàdàn iṣẹ́ ìwádìí rẹ̀ dá lórí àtúpalẹ̀ oògùn drug analysis pk/pd pharmacogenetics pharmacogenomics pharmaceutical analys... |
jair bolsonaro jair messias bolsonaro ojoibi kẹta 21 1955 lasan bi jair bolsonaro ni lowolowo aare ile brasil 38k lori aga lati kínní 1 2019 |
meet the neighbors awako ofurufu tabi pade alamuleti je episodu awakofurufu ninu amohunmaworan amerika agbejade ni ori afefe kompini ipolongo amerika abc ni ojo kerindinlogbon osu kesan odun 2012 olukotan ni dan fogelman ti adari si je chris koch ere na kogba iwuri ni awujo apapo ere yii alamuleti waye lati owo fogelma... |
9ice 9ice tí orúkọ rẹ jẹ alexander ábọ̀lọrẹ adégbọlá àkàndé wọ́n bí ni ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù ṣéẹ́rẹ́ ọdun 1980 ó jẹ́ olórin òǹkọ̀tàn-orin oníjó ọmọ orílẹ̀èdè nàìjíríà ó gbajúmọ̀ fún ìgbédègbẹyọ̀ rẹ̀ òwe lílò àti àgbékalẹ̀ orin rẹ̀ lọ́nà àrà ìdílé olórogún ni 9ice ti wá bàbá rẹ̀ ní ìyàwó márùn-ún àti ọmọ mẹ́sàn-àn ní ìl... |
alexa guarachi alexa guarachi je agba tenis ara tsílè |
ilé isé innoson olùpèsè okò ilé isé olùpèsè okò innoson ti orílè èdè nàîjíríà tí eon we àgékúrú rè sí ivm jé ilé isé tí ó n pèsè orísirísi ohun amurînà gégé bí okò akérò okò igbafé ní orílè èdè nàîjíríà ògbéni innocent chukwuma ni ó jé olùdásílè tí ó sì n se àmójútó ilé isé náà ní ìlú nnewi ní ìpínlè anambra ìdá ogórin... |
ojà àgbáláta badagry market ojà àgbáláta badagry market ni ojà tí ó tóbi jùlo ní agbègbè ìlú àgbádárìgì tàbí badagry ojà yìí ni ó wà ní ìtòsí àwon ilé ìfowó-pamó ubazenith àti ìfowó-pamó union ojà yìí ni ó jé wípé àwon èyà ègùn tí osé òòjó won jé isé oko síse ení híhun àgbon títà àti epo síse ni ó wópò tí ó n nájà náà ... |
sheik muyideen àjàní bello sheik muyideen àjàní bello jé àfáà nlá oní wáàsí lójú ònà mùsùlùmí àti omo bíbí ìlú ìbàdàn ó jé omo àádórin odún ìgbé ayé rè sheik muyideen àjàní bello bèrè isé wáàsí ìta gbangba nígbà tí ó wà ní omo odún méwàá léyìn tí ó ti kó nípa ìmò alùkùránì lábé bàbá rè tí ó jé àfáà àgbà nílùú àgberígbe... |
ààre kúrunmí ìjàyè ààre kúrunmí ìjàyè jé jagun jagun alágbára akínkanjú àti òkan lára àwon akoni ìgbà ìwásè tí ó ní agbára ogbón àti oògùn púpò ó jé omo bíbí àti asíwájú tàbí adarí ìlú ìjàyè lásìkò tirè ní ìpílè òyó ní àsìkò 1831-1862 ìgbésí ayé rè ààre kúrunmí ni ó jé oníyàwó púpò tí ó sì lo òpò ìgbésí ayé rè lójú ogu... |
afrominettia afrominettia jẹ́ ọ̀wọ́ tàbí irú kòkòrò kékẹeré tí ó ń gúnyẹ̀ẹ́ tí ó sì jẹ́ ẹbí lauxaniidae |
àmì ẹ̀yẹ lámèyítọ́ fíímù nollywood àti ilẹ̀ adúláwọ̀ àmì ẹ̀yẹ lámèyítọ́ fíímù nollywood àti ilẹ̀ adúláwọ̀ jẹ́ ayẹyẹ tí ó má ń wáyé lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo lọ́dún fún àwọn òṣèré fíímù àti sinima àgbéléwò nílẹ̀ adúláwọ̀ wọ́n ti ń ṣé rí ní orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà láti ìgbà tí wọ́n ti da sílẹ̀ láti ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹ́jọ ọdún 2011 ... |
nollywood reinvented tàbí ìsọdọ̀tun isodotun nollywood ìsọdọ̀tun nollywood tàbí nollywood reinvented tí a tún mọ̀ sí nr jẹ́ pèpéle ẹ̀rọ ayélujára t́i wọ́n dá sílè ní ọdún 2011 pèpéle yí wà fụ́n ìṣàgbéyẹ̀wò àwọn fiímù àti sinimá ọlọ́kan ò jọ̀kan ó tún fúni níròó nípa àwọn fíímù àwọn òṣèré àti àwọn ènìyàn míiràn pẹ̀lú òu... |
àwọn obìnrin tí ko wọ́pọ̀ àti àwọn yoku uncommon women and others àwọn obìnrin tí ko wọ́pọ̀ àti àwọn yoku ọdún 1977 jẹ́ eré àkọ́kọ́ tí gbajúgbajà ònkọ-eré-orí itage omo ile amẹ́ríkà ni sentury ogun wendy wasserstein |
igi ose ìgí oṣè jẹ́ igi tí ó wọ́pọ̀ láàárín àwọn elédè yorùbá ní ìpínlẹ̀ kwara |
èka ètò ìdájọ́ ìpínlẹ̀ èkó èka ètò ìdájọ́ ìpínlẹ̀ èkó jẹ́ ọ̀kan nínú ẹ̀ka mẹ́ta ti ìjọba ìpínlẹ̀ èkó tí ó wà lábẹ́ ìwé òfin ní orílẹ̀ èdè nàìjíría àti òfin tí ìjọba ti ìpínlẹ̀ èkó |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.