raw_text
stringlengths
2
128k
food and drug administration
david woodard david woodard ẹni tí a bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹrin odun 1964 6-04-1964 jẹ ọmọ amẹ́ríkà akọwe ati olùdaríorin
article for the wikipedia guidelines see and to start a wikipedia article see article or articles may refer to
omo yorùbá àwon omo yorùbá àwọn ọmọ yorùbá ń jẹ ẹ̀yà tó ń gbé ní gúúsù ìwọ̀ oòrùn àti àríwá apa àrin nàìjíríà àti gúúsù pẹ̀lú apa àrin benin lápapọ̀ àwọn agbègbè yí ń jẹ ilẹ̀ yorùbá èyí tó pọ̀ jù nínú àwọn ọmọ yorùbá ń gbé ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà níbẹ̀ wọn jẹ okanlelogun nínú ọgọ́rùn-ún àwọn ará nàìjíríà àwọn ọmọ yorùbá...
8 flora 8 flora àmì-ìdámọ̀ jẹ́ pálánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
ènìyàn
chuck mccann charles jonathan thomas chuck mccann september 2 1934 april 8 2018 je osere ara amerika
william bliss baker william bliss baker ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 1859 ogúnjọ́ oṣù kọkànlá ọdún 1886 jẹ́ ọmọ bíbí ìlú amẹ́ríkà tí ó jẹ́ oníṣẹ́ ọnà tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ọnà ṣíṣe ní àkóko tí ilé ìwé hudson river ń kó'gbà wọ'lé baker bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ọdún 1876 ní national academy of design níbi tí ó ti kọ́ ẹ̀kó...
michelle creber michelle nicole creber september 7 1999 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà
r lee ermey ronald lee ermey march 24 1944 april 15 2018 je osere ara amerika
tristan thompson tristan trevor james thompson ojo ibi ojo ketala osu keta odun i991 je omo bibi ilu canada ti o n ere idaraya ti boolu alafowogba-sinu-awon fun awon cleveland cavaliers ti national basketball association nba o gba ere idaraya yi fun saa kan ni ile iwe giga texas ki a to gba wo'le si owo kerin ti gbogbo...
ionuț silaghi de oas ionuț silaghi de oaș count de szilágyi-oaş ti a bi ni oṣù 16 1990 jẹ olorin ilu romania olugba ti awọn eniyan orin akọwe ati onisegun o jẹ olori orilọwọ ti idile ọlọgbọn szilágyi-oaş ati akowe agba lọwọlọwọ ti ansamblul oaşul o jẹ ile-iwe giga ti imọ imọ-ẹrọ ti cluj-napoca ati ti university of babe...
wale ogunyemi olóyè wale ogunyemi ofr oṣù ògún ọdún 1939 sí oṣù ọ̀pẹ ọdún 2001jẹ́ àgbà-ọ̀jẹ̀ eléré onísẹ́ òṣeré ògbóǹtarìgì ọ̀ǹkọ̀tàn eré onísẹ́ àti onímọ̀ èdè yorùbá ọmọ orílẹ̀èdè nàìjíríà yoruba ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé -ayé ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé ayé ọjọ́ kejìlá oṣù ògún ọdún 1939 ni wọ́n bí i sí ní ìlú ìgbájọ ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun a...
olufemi bamiro olufemi adebisi bamiro je ojogbon ninu imo-ero sayensi o si je oga-agba ana fun ile eko giga fasiti ti ilu ibadan ibere igbe aye ati eko a bi olufemi ni ojo kerin-din-logun osu kesan odun 1947 ni ilu ijebu-igbo ipinle ogun o lo si ile iwe girama molusi ni ijebu-lgbo ati ile iwe girama ti ijoba ni ilu iba...
segun adewale aeroland ọ̀túnba ṣẹ́gun adéwáléti gbogbo eniyan mo si segun aẹṛ́oland ti a bi ni ojo keedogun sukarun odun 1966 je ogbontarigi onisowo eleyinjuanu ati oloselu ibere pepe ni ilu eko o si je omo bibi ebiklei ti nijpionleba ibile ijero ni ipinle ekit i o wa ni apa guusu iwo-oorun naijiria oun si ni asoju fun...
lawrence anini lawrence nomanyagbon anini c 1960 march 29 1987 jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè nàjíríà tí ó jẹ́ adigun-jalè aṣèrùbàlú ilẹ̀ ìbìní benin ní ọdún 1980s òun pẹlú abẹ́sinkáwọ́ rẹ̀ moday osunbor ìjọba mú lawrence aníní látàrí àwọn ìwà ìbàj̣ẹ́ rẹ̀ wọ́n sì paá ìgbésí ayé rẹ̀ wọ́n bí lawrence aníní ní abúlé kan tí kò ju ǹkan...
omupo omupo tabi omu-ipo je ilu ad'ayeba ti o je mo igbomina ni ipinle kwara o je okan lara awon ilu ti o l'okiki ni ijoba ibile ifelodun o wa ni agbegbe guusu-ila oorun ipinle naa oun ni olu-ilu fun agbegbe merin-le-logbon ti o wa ni adugbo omupo oun tun ni olu-ilu agbegbe omupo/idofian ni ijoba ibile ifelodun oun kan...
rodney joseph johnson rodney joseph johnson october 24 1965 - september 21 2006 jẹ́ agbófin ró lábé ilé iṣé ̣ọlọ́pàá houston ẹni tí ó lo ọdú mẹ́rìnlá 14 years pẹ̀lú ilé iṣẹ́ nàà ṣáajú ìpapòdà rẹ̀ lẹ́nu iṣẹ́ ni ́ọjọ̣́ kọ̣kànlé-lógún oṣù kẹ̣́jọ ọdún 2006 juan leonardo quintero tó jẹ́ ẹni tó gbònà àìtọ́ wọ ilẹ̀ mexico lẹ́...
bimbo akintola bímbọ́ akíntọ́lá tí wọ́n bí ní ọjọ́ kàrún-ún oṣù karùn-ún ọdún 1970 jẹ́ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìbèrè ìgbé ayé àti èkó rè wón bí akíntôlá ní ojó karùn ún osù karùn-ún odún 1970 bàbá rè jé omo bíbí ìpínlè oyo tí ìyá rè sì jé omo bíbí ìpínlẹ̀ edo ó lo sí ilé-ìwé alákóbèrè ti àwo...
doda dorota rabczewska ojoibi 15 february 1984 je osere ara orile-ede poland
tego calderon tegui calderon rosario ojoibi february 1 1972 jẹ puerto rican rapper ati reggaeton singer
dharius alan alejandro maldonado tamez ojoibi september 24 1984 to gbajumo pelu oruko ori itage re dharius jẹ mexican rapper dharius gbajumo be rapper lati gangsta rap
akínwùmí iṣọ̀lá ọ̀jọ̀gbọ́n akínwùnmí ìṣọ̀lá ni a bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣùkejìlá ọdún 1939 tí ó sì tẹ́rí gbaṣọ ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kejì ọdún 201824 december 1939 17 february 2018 ni ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èd̀e nàìjíríà ó sì tún jẹ́ olùkọ̀tàn òṣèré-orí-ìtàgé olùgbáṣà lárugẹ àti onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ó di ìlú-mọ̀ọ́ká jákè jádò...
peter fatomilola wọ́n bí peter fátómilọ́lá' ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kínní ọdún 1946 ó jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀-èdènàìjíríà ó sì jẹ́ òṣèré orí ìtàgé olùkọ̀tàn akéwì àti ògúná gbòǹgbò níbi ká kọ eré-oníṣe playwright ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀ wọ́n bí peter fátómilọ́lá ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kínní ọdún 1946 sí ìjọba ìbílẹ̀ ìf...
ọlátúbọ̀sún ọládàpọ̀ ọlátúbọ̀sún oládàpọ̀ tí a mọ̀ sí túbọ̀sún ọládàpọ̀ tàbí odídẹrẹ́ ayékòótọ́ - odídẹrẹ́ asọ̀rọ̀-sọ-bótò wọ́n bí ni ọjọ́ kọkàndínlógún òṣu ọ̀wẹwẹ̀akéwì-alohùn jẹ́ akéwì-alohùn yorùbá òǹkọ̀wé olótùú orin atọ́kùn lórí rédíò sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ àti olùwádìí láti orílẹ̀èdè nàìjíríà tí púpọ̀ nínú àwọn olùgbọ́ rẹ̀...
fermín iv fermín iv caballero elizondo ojoibi december 1974 jẹ mexican rapper fermín gbajumo be rapper lati gangsta rap
duro ladipo dúró ládipọ̀ 19311978 jẹ́ ọ̀kan lára àwon ògúná gbòngbò olùkọ̀tàn eléré oníṣe yorùbá tí ń dátó lẹ́nu ìgbín ní ilẹ̀ adúláwọ̀ lẹ́yìn ìmúnisìn àwọn òyìnbó àwọn ìwé àpilẹ̀kọ rẹ̀ dá lórí èdè yorùbá ̀ó kó gbogbo ohun àmúyẹ àṣà yorùbá bí tàwọ̀n àkoni ìgbà ìwáṣè nínú ọ̀pọ̀ ìwé àpilẹ̀kọ rẹ̀ ní èyí tí ó ṣàyípadà rẹ̀ ...
joseph fọláhàn ọdúnjọ joseph fọláhàn ọdúnjọ 19041980 jẹ́ ogbóntagì òǹkọwé olùkọ̣́ àti olóṣèlú tí ó gbajúmọ̀ fún àpilẹ̀kọ lítíréṣọ̀ yorùbá àwọn ọmọdé ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí ọdúnjọ ní ìlú ìbarà abéòkúta ní ọdún 1904 ó lọ sí ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti 'st augustine primary school' ní abẹ́òkúta lẹ́yìn tí ó sì tún ...
lagos island ìsàlẹ̀ èkó lagos island jẹ́ àárín gbùngbùn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìpínlẹ èkó ó jẹ́ ọ̀kan lára ìjọba ìbílẹ̀ tí wọ́n pín ìpínlẹ̀ èkó sí nínú ètò ìkànìyàn tó wáyé ní ọdún 2006 nílẹ̀ nàìjíríà ìjọba ìbílẹ̀ náà ni ìwọ̀n èrò tó pọ̀ tó 209437 ní agbègbè tí kò ju ìwọ̀n ibùsọ̀ 87 km² ìjọba ìbílẹ̀ ìsàlẹ̀ èkó ló kó ìlàj...
lola ogunnaike lọlá ògúnnáìkè jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tún jẹ́ ọmọ ilẹ̀ amẹ́ríkà american tí ó jẹ́ amúlùúdùn àti oníròyìn ní ilẹ̀ amẹ́ríkà ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí lọlá ní ojo ketala osu kesan odun 1975 september 13 1975 ní ilu new york city amo awon obi re mejeji je omo orile ede naijiria o jade nile ek...
lọlá ògúnnáìkè lọlá ògúnnáìkè jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tún jẹ́ ọmọ ilẹ̀ amẹ́ríkà american tí ó jẹ́ amúlùúdùn àti oníròyìn ní ilẹ̀ amẹ́ríkà ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí lọlá ní ojo ketala osu kesan odun 1975 september 13 1975 ní ilú new york city àmọ́ àwọn òbí rẹ̀ méjèjì jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó jáde níl...
femi fani-kayode dafidi oluwafemi itumo eni ti olúwa feran adewunmi abdulateef fani-kayode je oloselu ni orile-ede naijiria onkowe a fi-oro-dara ati agbejoro o je omo egbe oselu ti o nse ijoba pdp o fi igba kan dara po mo egbe alatako apc ki o to pada si egbe pdp ni osu kefa odun 2014 bi o tile je pe awon ebi re wa lat...
ààtò àwọn fíímù ilé nàìjíríà èyí ni ààtò àwọn fíímù tí wọ́n ṣe ní orílẹ̀ èdènaijria list of films produced àti ọdún tí wọ́n gbé wọn jáde
sade baderinwa wọ́n bí fọláṣadé ọláyínká bádérìnwá tí wọ́n mọ̀ lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀ sí ṣadé bádérìnwá /ˈʃɑːdeɪ ˈbɑːdərɪnwɑː/ shah-day bah-dər-in-wah ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹ́rin 1969 born april 14 1969 jẹ́ olùdarí ètò ní orí wabc ìkànì kéje channel 7 bákan náà ni ó tún ṣe amúgbá-lẹ́gbẹ́ lórí ètò olósẹ̀-ọ̀sẹ̀ pẹ̀lú diana willia...
ṣade baderinwa wọ́n bí fọláṣadé ọláyínká bádérìnwá tí wọ́n mọ̀ lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀ sí ṣadé bádérìnwá /ˈʃɑːdeɪ ˈbɑːdərɪnwɑː/ shah-day bah-dər-in-wah ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹ́rin 1969 born april 14 1969 jẹ́ olùdarí ètò ní orí wabc ìkànì kéje channel 7 bákan náà ni ó tún ṣe amúgbá-lẹ́gbẹ́ lórí ètò olósẹ̀-ọ̀sẹ̀ pẹ̀lú diana willia...
gabriel okara wọ́n bi gabriel imomotimi okara ni ojo kerinlelogbon osu kerin odun 1921 born 24 april 1921 eni ti won bi ni bumoundi yenagoa bayelsa state o je akewi ati olukotan omo orile ede naijria o je okan lara awon akewi igbalode modernist poet of anglophone africa ile alawo dudu ti o n so geesi won mo gabriel lat...
solomon babalọlá solomon adébóyè babalọlá ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù ọ̀pẹ ọdún 1926 ó kú ní ọjọ́ kẹèdógún oṣù kèjìlá ọdún 2008 december 17 1926- december 15 2008 ní ilú ìpetumodù ní ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ olùkọ́ akéwì àti onímọ̀ ìgbésí ayé rẹ̀ ọ̀jọ̀gbọ́n solomon adébóyè babalọlá jẹ̀ ọmọ ìdí...
femi falana fẹ́mi fálànà san senior advocate of nigeria jẹ́ agbẹjọ́rò àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn ọmọ orílẹ̀ èdè̀ nàìjíríà tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹẹ̀dógbọ̀n oṣu kejìlá ọdún 195830 december 1958 ó díje dupò gómìnà ní ìpínl̀ẹ èkìtì ní ọdún 2007 ṣùgbọ́n ó pàdánù ìbò náà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú ncp national conscience party tí ó ti fì...
public holidays in nigeria nigeria
ijo anglika ìjọ ánglíkà ìjọ ánglíkà jẹ́ ìjọ tí o tóbi ṣe ìkẹrin nínú àgbáríjọ pọ̀ àwọn ọmọ lẹ́yìn krístì káàkiri àgbáyé pẹ̀lú ọmọ ìjọ tí ó tó miliọ̣nu márun-lé-lọ́gọ́rin eniyan
àwọn àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi ile naijiria ile naijiria ni àwọn àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi to po àwọn àyájọ ọjọ́ ìsinmi tó ma ń yí padà lafikun orile ede naijiri ni awon ayajo ojo isinmi kan ti deeti won ma n yi lodoodun
razaq okoya rasaki akanni okoya ni wọ́n bí ní ìpínlẹ̀ èkó ni ọjọ́ kejìlá oṣù kìíní ọdún 1940 12 january 1940 ó jẹ́ gbajúgbajà ìlúmọ̀ọ́kà oníṣòwò olówó tabua tí ó ní ilé iṣẹ́ púpọ̀ aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ razaq ọkọ́ya kẹ́kọ̀ọ́ àkóbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ nílé ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ tí ansar-un-deen òkè pòpó ní ìpínlẹ̀ èkó òun ni aláṣẹ àti ...
arun hiv/aids ni naijiria lásìkò 2014 ní nàìjíríà hiv wọ́pọ̀ láàrín àwọn ọ̀dọ́ tó ti bàlágà tó ti tó ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dógún sí ọ̀kandị́nláàdọ́ta jẹ́ ìdá 317 ilẹ̀ nàìjíríà ni ó gbé ipò kejì nínú àwọn tí ó n semi pẹ̀lú àrùn hiv àrùn hiv di àjàkálẹ̀ tí ó sì pọ̀ ju ara wọn lọ ní agbègbè sí agbègbè làwọn ìpínlẹ̀ kan ti tàn kál...
wahab iyanda folawiyo won bi oloye wahab abdulwahab iyanda folawiyo ni june 16 1928 o ku ni june 6 2008 o je onisowo omo orile ede naijiria ti o si je oluran-lowo fun awon eniyan ni odun 1957 o da ile ise yinka folawiyo sons kale eyi ti o je ipile fun awon ogooro ile ise ree to ku won bi iyanda wahab folawiyo ni ipinle...
gladys knight gladys maria knight ojoibi may 28 1944 to gbajumo bi empress of soul iyaluaye orin soul je akorin olukoweorin ato osere ara amerika o gba ebun grammy ni emeje knight gbajumo fun awon ayori orin to gbejade ni igba ewadun 1960s ati 1970s fun ile-ise agbeorinjade motown ati buddah records pelu egbe olorin re...
taye taiwo taye ismaila taiwo jẹ́ àgbá bọ́ọ̀lù ọmo orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó gbá bọ́ọ̀lù owó ẹ̀yìn fún orílè-èdè nàìjíríà àti fún ẹgbẹ́ àgbágbọ́ọ̀lù ropí wọ́n bi ní ọjọ́ kẹrin dínlógún oṣù kẹrinapril 16 ọdún 1985 iṣẹ́ rẹ̀ ní àwọn ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù lobi stars lẹ́yìn tí ó ti lo ọdún kan nínú ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù nàìjíríà divi...
ona marose eko-badagry opopona marose agbadarigi je oruko ibile kan ti won fi n pe ona marose naa ninu transwest african coastal highway titi marose naa lo si ipinle eko ti o si ja mo ilu dakar senegal isatunse ona marose naa bere ni pereu ni odun 2010 nigba ti awon atunse naa ba pari ona marose eko yoo di mewaa dipo o...
ajodun odun badagry ọdún ìbílẹ̀ àgbádá-rìgì jẹ́ ayẹyẹ tí wọ́́n ma ń ṣe ní ẹ̀ẹ̀kan ṣoṣo lọ́dun tí ó ma ń wáyé ní ìlú àgbádá-r̀ig̀i badagry tí ó jẹ́ ìlú ńlá kan ní ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà àjọ african renaissance foundation arefo ló ma ń ṣ̀agbátẹr̀u ayẹyẹ náà àwọn èt̀o inú ayẹyẹ náà má ń fi ip̀o ìlú náà hàn ní ...
àtòjọ àwọn òrìṣà yorùbá àwọn wọ̀nyí ni àwòn òrìṣà ilẹ̀ yorùbá òrìṣà tó ga jù ọlọ́run elédùmarè ní orúkọ mẹ́ta tí yorùbá má ń pèé àwọn ni
list of yoruba deities
abacavir abacavir abc jẹ́ oògùn kòkòrò àjẹsára tí ó ń dáàbò bo àwọn ọmọ ogun ara tí ó sì tún ń pa kòkòrò àìfojúrí hiv/aids run nínú àgọ́ ara ènìyàn a lè lo oògùn yí gẹ́gẹ́ bí a ṣe ń lo àwọn oògùn tí ó ń gbógun ti àrùn àìfojúrí hiv/aids ba kan náà ni a sí lè da lò lóun nìkan pẹ̀lú ìtọ́ni dókítà wọn a máa fi omi lòó tàbí...
sheik adam abdullah al-ilory seik adam abdullah al-ilory ni wọ́n bí ní ọdún 1917-1992 sí ìdílé ṣéù abdul baqi al-ilory ó jẹ́ àṣáájú onímọ̀ ìjìnlẹ̀ nínú èsìn islam ní orílẹ̀ èdè benin-nàìjíríà ó jẹ́ ẹni tí ó tẹ̀lé ìlànà imam maliki tí ó sì jẹ́ òǹkọ̀wé ìmọ̀ oríṣiríṣi nínú èdè lárúbáwá arabic author ó tún jẹ́ oní súfi ní ...
shina peters sir ṣínà peters tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹẹ̀dọ́gbọ̀n oṣù kẹ́ta ọdún 1958 30 may 1958 ní ó jẹ́ olórin jùjú ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà ìgbésí ayé rẹ̀ wọ́n bí olúwásínà àkànbí peters ní ìpínlẹ̀ ògùn peters bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ láti ìgbà èwe rẹ̀ nígbà tí ó ma ń ṣeré pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ lábé orúkọ olúṣínà àti àwọn ọmọ ìy...
awon antwan wiggins tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹ́ta ọdún 1980 march 6 1980 ní ìlú brooklyn jẹ́ ọ̀kọrin hip hop ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà orúkọ tí wọ́n mọ̀ọ́ pẹ̀lú rẹ̀ ni 'awon' ní ọdún 2014 ó dá ile- iṣẹ́ orin don't sleep kalẹ̀ pẹ̀lú àjọṣepọ̀ phoniks 'awon' ti kọrin pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olórin hip hop ilẹ̀ ̀amẹ́ríkà b...
sade solapur district sade jẹ́ abúlé kan ní ìlú karmala taluka tí solapur district ní ìpínlẹ̀ maharashtra ilẹ̀ india tìbú tòró rẹ̀ sade tó ìwọ̀n ẹgbẹ̀rún mẹ́ta àti ìgbà àti mẹ́rìndín-láàdọ́rin tí ó sì ní ilé ìgbé tí ó tó 1077 lásìkò ìkànìyàn tí ó wáyé ní ọdún 2011 2011 census of india sade ni ó ní iye ènìyàn tí ó tó 45...
adeniran ogunsanya college of education adeniran ogunsanya college of education tí àgékúrú rẹ̀ ń jẹ́ aocoed jé ilé-ẹ̀kó gíga higher education tí ó wà ní ìlú ọ̀tọ̀-àwórì lábẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ ọ̀jọ́ ìpínlé̀ èkó ilé- ẹ̀kọ́ adéníran ògúnsànyà ń ṣètò ìmọ̀ ìkọ́ni gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ tí ó sì ń pèsè ìwé ẹ̀rí 'nigeria certificate in ...
ọ̀tọ̀-àwórì ọ̀tọ̀-àwórì je ijoba idagba-soke agbegbe ijoba ibile ojo ti o wa ni opopona marose èkó si agbada-rigi
niyi adeolokun
níyì adéolókun níyì adéolókun tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹ́ta oṣù kọkànlá ọdún 1990 3 november 1990 jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù rugby fún irish rugby union ó ń gbá fún wọn gẹ́gẹ́ bí onígun winger adéolókun ló tún ń gbá rugby fún ikọ̀ connacht ní pro14 ó dara pọ̀ mọ́ connacht ní ọdún 2014 láti ilé-ẹ̀kọ́ 'trinity college' lásìkò tí ó fi w...
àtòjọ àwọn olórin ilẹ̀ nàìjíríà èyí ni àtòjọ àwọn olórin tó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà àwọn tí wọ́n jẹ́ ìlú mọ̀ọ́ká nìkan ni a kó jọ sí abẹ́ ààtò yí ẹ lè wo àtòjọ ìpín àwọn orin orílẹ̀ èdè náà ní ẹ̀ka 'nigerian musical groups'
òjó adé òjó adé ni wọ́n bí ní ojo kewa osu kewa odun 1959 ó jẹ́ olórin olùkọ orin-ẹ̀mí gósípẹ́ẹ̀lì àti olùṣọ́ àgùtàn ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀ wọ́n bi ní ọjọ́ kẹ́wàá oṣù kẹwàá ọdún 1959 october 10 1959 ní ìlú ìkeji-ilé ìlú ńlá kan ní ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun ó kẹ́kọ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ st judges anglican church tí ...
wasiu alabi pasuma wọ́n bí wasiu àlàbí pasuma ní november 27 1967 sí mushin ní ìpínlẹ̀ èkó tí bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ kwárà òun náà ni wọ́n tún ń pè ní ògánla ó jẹ́ òṣèré ọ̀kọrin fújì ó sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjìríà iṣẹ́ òòjọ́ rẹ̀ pasuma di gbajú-gbajà olórin fújì ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà nígbà tí ó ṣe àwo orin tó sọọ́...
saheed balogun saheed balógun ni wọ̣́n bí ní ọjọ́ karùún oṣu kejì ọdún 1967 february 5 1967 ní ìpínlẹ̀ kwara ó jẹ́ gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé olùgbéré jáde adarí eré àti olùṣe fíímù ilẹ̀ nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ àti iṣẹ́ rẹ̀ wọ́n bí saheed ní ìpínlẹ̀ kwara tí ó jẹ́ north central nigeria ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ ọ̀...
kwara state polytechnic kwara state polytechnic jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo-nìṣe ilẹ̀ nàìjíríà tí olórí ìjọba ológun ìpínlẹ̀ kwara tẹ́lẹ̀ ọ̀gágun col david bámigbóyè dá sílẹ̀ ní ọdún 1973 ní wọ́n kéde rẹ̀ lẹ́yìn tí wọ́n ti pinu láti dá ilé-ẹ̀kọ́ náà sílẹ̀ sí ìpínlẹ́̀ kwara lọ́dún 1971 ilé-ẹ̀kọ́ náà ló wà ní ìl...
list of nigerian highlife musicians eleyìí ni àtòjọ̀ àwọn olórin highlife ilẹ̀ nàìjíríà tí wọ́n gbajúmọ̀ jùlọ ní àtò a - y oríṣiríṣi ẹ̀yà tàbí oníran ìran orin ló wà lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ni èyí tí a ti rí orin fújì jùjú apala wéré àti highlife bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ghana ni orini highlife ti ṣẹ̀ wá tí ó fi tàn dé gbogbo il...
àtòjọ̀ àwọn olórin highlife ilẹ̀ nàìjíríà eleyìí ni àtòjọ̀ àwọn olórin highlife ilẹ̀ nàìjíríà tí wọ́n gbajúmọ̀ jùlọ ní àtò a - y oríṣiríṣi ẹ̀yà tàbí oníran ìran orin ló wà lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ni èyí tí a ti rí orin fújì jùjú apala wéré àti highlife bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ghana ni orini highlife ti ṣẹ̀ wá tí ó fi tàn dé gbo...
jenny slate jennifer sarah jenny slate march 25 1982 jẹ́ òṣèré ará amẹ́ríkà
délé òjó delédà òjó jẹ́ olórin jùjú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ọ̀pọ̀ ènìyàn gbà wípé òun ni ó tan ẹ̀yà orin náà kálẹ̀ iṣẹ́ orin rẹ̀ délé òjó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin rẹ̀ ní pẹrẹu nígbà tí ó ṣalábàá-pàdé olórin kan tí ó ń jẹ́ victor ọláìyá ẹni tí ó gba délé sí inú ọmọ ẹgbẹ́ akọrin rẹ̀ ní ọdún 1961 òjó dá ẹgbẹ́ òṣèré akọrin tírẹ...
national democratic coalition nigeria national democratic coalition nadeco ni wọ́n dá sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù karùún ọdún 1994 may 15 1994 láti ọwọ́ broad coalition of nigerian democrats tí ó pè ìjọba ológun tí sani abacha láti kúrò lórí àléfà fún ẹni adìbòyàn june 12 1993 ìyẹn m k o abíọ́lá àwọn afẹ̀hónú hàn olóṣè...
àwọn àtòjọ ẹgbẹ́ òṣèlú ilẹ̀ nàìjíríà èyí ni àtòjọ àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú ilẹ̀ nàìjíríà
unity party of nigeria unity party of nigeria upn ló ti fìgbà kan jẹ́ ẹgbẹ òṣèlú ilẹ̀ nàìjíríà tẹ́lẹ̀ tó lààmì laaka ní àpá ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ nàìjíríà lásìkò ìjọba àwa-arawa ẹlẹ́kejì second republic ní ọdún 1978-1983 ẹgbẹ́ òṣèlú náà ló dá lórí ipò aṣáájú ológbèé ọbáfẹ́mi awólọ́wọ̀ ẹni tí ó ti fìgbà kan jẹ́ ìlú-mọ̀ọ́ka ol...
monte águila tsile monte águila jẹ ilu kan ni tsile
ile ominira ilẹ̀ omínìra jẹ́ ilé-iṣẹ́ alájà márùndínlọ́gbòn tí wà ní ìwọ̀ oòrùn tafawa balewa square ní oníkan ní ìlú èkó ìjọba orílẹ̀-èdè britain ní ó ṣe ìdáwọ́lé yìí nípa kí ó lè ìjẹ́rísí òmìnira orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 1960 konkere ti won ti fi agbara kun ni won fi ko ile yi inu ile yi ni ile olori ise olugbega ...
benin pendant mask
oke ila
òkè ìlá òkè-ìlá òràngún tí a ma n gé kúrú sí òkè-ìlá jẹ́ ìlú àdàyé bá ní ìhà gúsù-iwọ̀ oòrùn orílẹ̀-èdè nàíjíríà tí o ti fi ìgbà kan jẹ́ olú-ìlú ẹ̀yà àwọn igbomina-yoruba tí a n fi orúko kan an naa pe òkè-ìlá jẹ́ ọ̀kan l'ára àwọn ìlú tí o wa ní ìpínlẹ̀ ọṣun ní orílẹ̀-èdè nàíjíríà òkè-ìlá wa ni apá ìhà àríwá ilà-oòrùn i...
àwo̩n ò̩jò̩gbò̩n nínú èdè àti lítírés̩ò̩ yorùbá àwo̩n ò̩jò̩gbò̩n nínú èdè àti lítírés̩ò̩ yorùbá professors of the yorùbá linguistics language literature culture s/n oruko yunifasiti 1 emeritus professor adeboye babalola university of lagos 2 emeritus professor ayo bamgbose university of ibadan 3 professor oladele awobu...
tosin lawson tosin lawson jẹ́ onímọ̀ nipa oge àti olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ tí wọ́n ń pè ní african design tosin kàwé gboyè àkọ́kọ́ ní unifásítì ti nottingham nibi tí ó ti kọ́ nípa ìmọ̀ bí a ṣe lè pèlò nka ó jẹ́ ìkan lára àwọn tí ó ń gbé oge ìbílẹ̀ larugẹ iṣẹ́ àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ ṣe ni ẹ̀gbà ọrùn tí a fi àǹkárá ṣe ṣẹ̀ṣọ́ sí ...
lere paimo lér̀e pàímọ́ ofr ni wọ́n bí ní oṣu november ọdún 1939 ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà àti òṣèré orí-ìtàgé olù-kọ̀tàn eré orí-ìtàgé àti adarí eré orí-ìtàgé ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀ wọ́n bí lérè pàímọ́ ní ọdùn 1939 ní ìlú ògbómọ̀sọ́ tí ó jẹ́ ìlú ńlá kan ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ilẹ̀ nàìjíríà ìṣẹ́ rẹ̀ gẹ̀gẹ̀ bí òṣẹ̀ré ó bẹ...
national arts theatre national arts theatre je ogan gan ibi ipate isere ori-itage ile naijiria ile igbafe naa ni o kale si agbe gbe iganmu ni ijoba ibile surulere ni ipinle eko won ko gbongan isere yii pari ni odun 1976 fun ipalemo ayeye akojopo ile adulawo meri ti festac festival of arts and culture ni odun 1977 awon ...
nigeria advance party egbe oselu nigeria advance party nap ni won da sile ni asiko isejoba awa arawa elekeji second nigerian republic ni ile naijiria ti o si foruko sile fun eto idibo odun 1983 eni ti o je olori egbe oselu naa ni tunji braithwaite ti o je agbejoro won faye gba egbe naa lati fa oludupo ti yoo kopa ninu ...
ijora lagos ijora je okan lara awon agbegbe ilu eko ni orile ede naijiria itan ijora je ile ira omi swampy and water-logged ti awon ti won n bo lati lagos island ko ni le de ibugbe won aya fi ki won wo oko oju omi idasile ibudoko oko oju irin the establishment of a railway terminus si ido ti o je ileto kan ti o wa ni i...
àtòjọ àwọn ilé-ìfowópamọ́sí ilẹ̀ nàìjíríà èyí ni àtòjọ àwọn ilé-ìfowópamọ́ ilẹ̀ nàìjíríà tí wọ́n tún gbòǹtẹ̀ ìdánimọ̀ àgbáyé ní tẹ̀lé-ǹ-tẹ̀lé èyí ni àtòjọ àwọn ilé-ìfowópamọ́ ilẹ̀ nàìjíríà tí wọ́n tún gbòǹtẹ̀ ìdánimọ̀ àgbáyé ní tẹ̀lé-ǹ-tẹ̀lé èyí ni àtòjọ àwọn ilé-ìfowópamọ́ ilẹ̀ nàìjíríà tí wọ́n tún gbòǹtẹ̀ ìdánimọ̀ àg...
àtòjọ àwọn ilé-ìfowópamọ́sí ilẹ̀ ẹ́gíptì eyi ni atojo awon ile ifowo-apmo olokowo ile egypt ni tele n tele in
eyi ni atojo awon ile ifowo-apmo ile egypt
atojo awon ile ifowo-pamo ile naijiria
shola allyson shola allyson-obaniyi lédè yorùbá ṣọlá allyson-ọbáníyì jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó jẹ́ akọrin ẹ̀mí soul àti ìbílẹ̀ ó sì tún jẹ́ olùkọ́ orin ó di gbajú-gbajà akọrin pẹ̀lú ìkan lára àwọn orin rẹ̀ tí ó pè ni ejì òwúrọ̀ ní ọdún 2003 orin yìí sì tún jẹ́ orin àgbàsílẹ̀ fún fíìmù kan tí ó dẹ̀ pè ni ejì òwúr...
gani adams iba gàníyù adams t́i fi ìgbà kan jẹ́ olórí ẹgbẹ́ ọmọ odùduwà tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí opc a bí ọ̀túnba ganiyu adam ní ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù kẹrin ọdún 1970 ó jẹ́ ajìjàngbara àti ààrẹ ọ̀nàkakaǹfò ìgbẹ́ ayé rẹ̀ wọ́n bí gani adams ni ọjọ́ kẹẹ̀dọgun oṣù kẹrin ọdún 1970 ní arigidi-akoko tí wọ́n pè ní àkókò north-west loca...
nestlé nestlé sa /ˈnɛsleɪ ˈnɛsəl ˈnɛsli/ tì a mó télè si /ˈnɛsəlz/ jẹ́ ilé-iṣẹ̀ aṣońjẹ ti orílè-èdè swiss tí olú-iléesé wọn wà ní vevey vaud switzerland ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ asońje tí ó tóbi jùlo ní àgbáyé bí a bá fi òṣùwòn owó pípa wolé àti awon òṣùẁòn mìíràn láti ọdún 2014
ilu mowo ilu mowo je ilu kan ni ijoba ibile agbadarigi ni ipinle eko lowolowo bayii kosi ojulowo baale ni ilu mowo nitori faakaja awon omo oye
ògbómòsọ̀
ògbómọ̀sọ́ ògbómọ̀sọ́ jẹ́ ìlú ní ìpínlẹ̀ ọ̀yo ní apá ìwò-oòrùn oriĺè-èdè nàìjíríaì a dá ìlú ògbómọ̀sọ́ sílẹ̀ ní 17th century àpapọ̀ iye àwọn ènìyàn tí ó wà níbè gẹ́gẹ́ ètò ìkànìyàn ọdún 2006 sọ jẹ́ 645000 yorùbá pó́ńbélé ni ọ̀pọ̀ àwọn òlùgbé ògbómọ̀sọ́ iṣẹ́ àgbẹ́ iṣu gbágùúdá àgbàdo àti ewé sìgá jẹ́ lára àwọn iṣẹ́ tó g...
badagry àgbádárìgì tí a kọ́kọ́ mọ̀ sí gbagle láti ìbèrè jẹ́ ìlú ẹ̀bádò àti ìjoba ìbílè ní ipínlè èkó lórílẹ̀-èdè nàìjíría àgbádárìgì gúnwà láàárín ìlú èkó àti orílẹ̣̀-èdè olómìnira benin èyí jásí wípé ó tún jẹ́ ìlú alálà nàìjíría àti orílẹ̣̀-èdè olómìnira benin ni sèmè gẹ́gẹ́bí àkọsílẹ̀ ètò ìkànìyàn ọdún 2006 àpapọ̀ iy...
moremi ajasoro
àtòjo àwon ìjoba ìbílè ìpínlè èkó pèlú ònkà orí kòòkan won
mọ́remí ájàṣoro mọ́remí àjàsorò jẹ́ akọnibìnrin kan gbòógì tó sì gbajúmọ̀ nínú ìtàn àwọn yorùbá lápá ìwọ̀-oòrùn áfíríkà móremí fẹ ọ̀kan lára ẹbí oduduwa ti ìtàn àdáyébá sọ pé ó jẹ́ babańlá àwọn yorùbá ìgbésíayé rẹ̀ mọ́remí jẹ́ olorì ọba ìlú ilé-ifẹ̀ omobíbí ìlú ọ̀fà ó jẹ́ aḳonibìnrin tó gbajúmò ní séńtúrì méjìlá sẹ́yìn...
mary slessor mary mitchell slessor ọjọ́ kejì oṣù kejìlá ọdún 1848 si ọjọ́ kẹtàlá oṣù kínní ọdún 1915 jẹ ajihinrere si orílẹ̀-èdè naijiria lati ilu scotland ní kété tí o dé orílẹ̀-èdè naijiria slessor bẹ̀rẹ̀ si kọ èdè efik ti o jẹ́ èdè ìbílẹ̀ níbẹ̀ nítorí ìmò ti o ni nipa èdè ìbílẹ̀ yi ati ìsẹ̀dá rẹ gẹ́gẹ́ bi ẹni ti o n...
ida s scudder dr ida sophia scudder ọjọ́ kẹsan oṣù kejìlá ọdún 1870 si ọjọ kẹta-lé-lógún oṣù karun ọdún 1960 jẹ ìran kẹta àwon ajínhìnrere oníwòsàn lati ilẹ india ti a n pe ni reformed church in america o fi aye rẹ jin fun gbígba àwon obìnrin ilẹ̀ india kuro ninu ìpọ́njú ati gbígbógun ti àwon àrùn bi buboniki oní'gbá-m...
adéyeyè enitàn ògúnwúsì
priscilla studd priscilla scilla studd saájú ọdún 1887 si ọdún 1929 omidan priscilla livingstone stewart jẹ́ ajíhìnrere ni ijọ alátẹnumó-ọmọ lẹ́yìn krístì o si jẹ ìyàwó ọ̀gbẹni charles studd a bi i ni lisburn l'ẹba belfast ni ìlú ireland eleyi ti o ti di apá ariwa ilẹ̀ ireland l'ode oni priscilla stewart gúnlẹ̀ ni ìlú ...