raw_text
stringlengths
2
128k
denzel washington denzel hayes washington jr ọjọ́ ìbí ọ̣jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1954 jẹ́ òṣèré àti olùdarí eré ọmọ ilẹ̀ amẹ́ríkà washington ti gba ẹ̀bùn oscar àti ẹ̀bùn wúrà róbótó ní ẹ̀méèjì
steve biko steve biko 18 december 1946 12 september 1977 je omo ile guusu afrika ti o lodi si eto eleyameya larin odun 1960 si ibere 1970
aisan down aisan down je aisan opolo ti n so awon to ba ni di ode a n pe loruko john langdon down eni ti o koko se alaye aisan yi ni odun 1866
nomba
nomba tosoro
nomba gidi
nomba odidi
nomba onipin
nomba adabaye
nomba tikosi
nomba akoko
ìmọ̀ ìsirò
èdè látìnì ede latini je ede indo-europe ayejoun ti won n so ni ile romu ati ni ileoba romu
èdè gríkì èdè gíríìkì jẹ́ èdè àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè gíríìsì àti kipru álífábẹ́ẹ̀tì wọn jáde láti inú phoenician script tí ó wá padà di ìkọsílẹ̀ fún èdè látìn cyrillic armenian coptic gothic àti àwọn ìkọsílẹ̀ mìíràn láti nǹkan bíi ẹgbẹ̀rún ọdún mẹ́ta sẹ́yìn ni wọ́n ti ń sọ èdè gíríìkì ní balkan peninsula ẹ̀rí àkọ́kọ́ tí w...
fránsì fránsì pípè /ˈfræns/ tabi /ˈfrɑːns/ fun ibise gege bi ile faranse olominira je orile-ede ni apa iwoorun europe to ni opolopo agbegbe ati erekusu ni oke okun ti won wa ni awon orile miran fransi je orile-ede onisokan olominira ti aare die ti bi o se n sise wa ninu ipolongo awon eto eniyan ati ti arailu
faranse
kameroon
cm cm je ti kameroon
goodluck jonathan goodluck jonathan ọjọ́ìbí 20 noveber belu1957 jẹ́ olósèlú ọmọ ilè nàíjíríà àti àare orílé èdè nàíjíríà láti may èbìbi 6 2010 ohun ní igbákejì àare ilè nàíjíríà sí àare umaru músá yaradua kí ó tó dibo fun gégé bí adìbó àare ni 9 february 2010 nítorí aìsàn tó dé ba yaradua mólè léyin ti yar'adua kú ní m...
ogun agbaye elekeji <ns>0</ns> <revision> <parentid>40817</parentid> <timestamp>2009-05-11t102739z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> </contributor> <comment>redirected page to ogun àgbáyé ẹlẹ́ẹ̀kejì</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format>
alicia keys alicia augello cook ojoibi january 25 1981 to gbajumo pelu oruko ori-itage re alicia keys je olusona olorin ati osere ara amerika
bob dylan bob dylan oruko ibi robert allen zimmerman ojo ibi may 24 1941 je olorin/akorin omo ile amerika
pi pi tabi π tabi pai jẹ́ ọ̀kan nínú oǹkà ìmọ̀ ìṣirò mathematics tó ṣe pàtàkì ó fé tó 314159 ó dúró fún ìpín ìyíká obirikiti mọ́ ìlà ìdáméjì rẹ̀
zambia orílẹ̀-èdè olómìnira zambia pípè /ˈsæmbiə/ jẹ́ orílẹ̀-èdè tileyika kan ni apaguusu afrika awon orílẹ̀-èdè tó súnmọ ni orílẹ̀-èdè olómìnira toseluarailu ile kongo ní àríwá tanzania ni ariwa-ilaorun malawi ni ilaorun mozambique zimbabwe botswana ati namibia ni guusu ati angola ni iwoorun oluilu re ni lusaka tó bùd...
apágúúsù áfríkà iha guusu afrika
ìwọòrùn áfíríkà ìwọ̀orùn áfríkà tàbí apáìwọ̀oòrùn afíríkà ní àgbègbè ilẹ̀ afíríkà tó sún mọ́ ìwòoòrùn jù lọ ní ilẹ̀ áfíríkà
ìlaòrùn áfríkà iha tabi apa ilaoorun africa jé ïhà tó sumo apa ilà oòrùn jù àwon orílè-ede tówà ní ìlà-oòrùn afrika ní tanzania kenya uganda rwanda burundi eritreaethiopia somalia comoros mauritius seychelles sudan djibouti eritrea madagascar malawi réunion somaliland ìlà-oòrùn afrika ní olùgbé to sumó 464911091 ni 202...
àrin áfríkà apa arin afrika
ọkọ̀ òfurufú ọkọ̀ òfurufú jẹ ọkọ oju-ọrun ti irinṣẹ jet engine n gbe fò loju ofururu oko ofurufu wa ni iwon ati ipele orisirisi on oniruuru iye apa ti o n gbefo loju orun a le fi oko furufu se ise ero kiko lati ibikan si omiran bakan naa ni awon omo ogun oju-orun ma n loo lati fi sise won gbogbo àwọn bàlúù yí náà ni àw...
nina simone nina simone oruko abiso eunice kathleen waymon february 21 1933 april 21 2003 je omo ile amerika akorin oluko orin atepiano atorin ati alakitiyan awon eto araalu to ko orin jazz simone fe di atepiano orin klasik bo se n sise lopo iru orin ti ninu won je klasik jazz blues soul folk rb gospel ati pop botileje...
ethiopia ethiopia je orile-ede ni agbegbe iha ìlàorùn áfríkà
jẹ́rmánì
jamani
rọ́síà rọ́síà pìpè ˈrʌʃə rọ́síà rossiya tabi orile-ede ìparapọ̀ rọ́sìà rọ́síà je orileijoba ni apaariwa eurasia o je orile-ede olominira sistemu aare die alasepapo to ni ipinle ijoba 83 rosia ni bode mo awon orile-ede wonyi latiariwaiwoorun de guusuilaorun norway finland estonia latvia lithuania ati poland lati egbe ka...
wikipẹ́díà l'édè yorùbá wikipẹ́díà l'édè yorùbá ni àgbéjáde wikipedia ní èdè yorùbá ó bẹ̀rẹ̀ ní osù kẹwàá ọdún 2002 lọ́wọ́lọ́wọ́ ó ní iye àyọkà àti àwọn oníṣe aforúkọsílẹ̀ wikipẹ́díà l'édè yorùbá ní wikipedia ẹ̀kẹta tótóbijùlọ nínú àwọn wikipẹ́díà l'édè áfríkà lẹ̀yìn èdè lárúwábá àti èdè swahili òhun ni wikipedia 105k ...
uniform resource locator uniform resource locator tabi url tabi universal resource locator alawari onaigbekele abamu je oro ti a n lo lori internet
url
ìmọ́lẹ̀ ìmọ́lẹ̀ tabi titanina
obáfẹ́mi awólọ́wọ
ede yoruba
ààrẹ ilẹ̀ nàìjíríà ààrẹ orílẹ̀-èdè olómìnira ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀ nàìjíríà president of the federal republic of nigeria tàbì ààrẹ ilẹ̀ nàìjíríà lásán ni olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba orílẹ̀-èdè olómìnira ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀ nàìjíríà ààrẹ ilẹ̀ nàìjíríà náà tún ni aláṣẹ pátápátá àwọn ológun nàìjíríà àwọn ará nàìjíríà ún dì...
umaru yar'adua
olusegun obasanjo
murtala mohammed
shehu shagari shehu usman aliyu shagari bíi ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọn oṣù keji ọdún 1925-2018 jẹ̣́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà àti ààrẹ ilẹ̀ nàìjíríà lati ọjọ́ kínni oṣù kẹwá ọdún 1979 títí di ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1983 nígbàtí àwọn ológun gba ìjọba ìgbé yawo shehu shagari fẹ́ ìyàwó mẹtaamina aisha àti hadi...
johnson aguiyi-ironsi johnson thomas umunnakwe aguiyi-ironsi ọjọ́ 3oṣù ẹ̀rẹ̀nà ọdún 1924 - ọjọ́ 29 oṣù agẹmọ ọdún 1966 jẹ́ ológun ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà lẹ́yìn tí ológun gba ìjọba ní ọjọ́15 oṣù ṣẹrẹ ọdún1966 aguiyi-ironsi di olórí orílẹ̀-èdè nàìjíríà títí di ọjọ́ 29 oṣù agẹmọ ọdún1966 nígbà tí wọ́n dìtẹ̀ sí ìjọba rẹ̀ ...
umuahia umuahia ni ìlú tí ó jẹ́ olú-ìlú ìpínlẹ̀ abia ní gúúsù ìlà oòrùn orílè-èdè nàìjíríà umuahia wà lọ́nà oju irin tí ó wà láàrin port harcourt àti ìlú enugu àwọn ẹ̀yà igbo ni ó wọ́pọ̀ ní umuahia umuahia ní olùgbé 359230 gẹ́gẹ́ bí àbáyọ rí ounka ènìyàn ọdún 2006 ní nàìjíríà ṣe fi léde àwọn ẹ̀yà igbo ni ó wọ́pọ̀ ní um...
biafra biafra tí a mọ̀ sí orílẹ̀-èdè biafra jẹ́ ìlú tó yapa kúrò nínú apá ìwọ̀-oòrùn áfíríkà tí ó gba òmìnira ní nàìjíríà láàárín ọdún 1967 títí di ọdún 1970 àwọn ẹ̀yà ìgbò ní apá ìlà oòrùn nàìjíríà ni wọ́n kún bẹ̀ fọ́fọ́fọ́ ọgbọ́n ọjọ́ oṣù èbìbí ọdún 1967 ni ológun àti gómìnà ẹkùn ìlà oòrùn c odumegwu ojukwu dá biafra...
ẹnúgu enugu je oluilu ipinle enugu ni ile naijiria
ogun abele nigeria ogún abẹ́lé ilẹ̀ nàìjíríà wáyé láàárín ọjọ́ kẹfà oṣù okúdù ọdún 1967 sí ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù ṣẹ́ẹ́rẹ́ tí a tún mọ̀ sí ogun nàìjíríà - biafra tàbí ogun biafra jẹ́ ogun abẹ́lé tí ó wáyé láàárín ìjọba nàìjíríà àti orílè-èdè biafra ìpínlẹ̀ tí ó fé dádúró tì ó ti fẹ́ gba òmìnira kúrò lára nàìjíríà ní ọdún 1...
ogun biafra
odumegwu ojukwu chukwuemeka odumegwu-ojukwu a bíi ní ọjọ́ kẹrin oṣù kọkànlá ọdún 1933 - ó sì kú ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 2001jẹ́ ológun àti òsèlú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tẹ́lẹ̀ ó fìgbà kan jẹ gómìnà ológun apá àríwá nàìjíríà lọ́dún 1966 oun ló ṣe égbátẹrù ogun abẹ́lé biafra fi tako ìjọba orile-ede nàìj...
mùsùlùmí musulumi je eni ti o ti gba esin islam
yola yola di olú-ìlú àti ìlú tí ó tóbi jù ní f ìpínlẹ̀ adamawa nàìjíríà ìlú náà wà ní olùgbé 336648 ní ọdun 2010 yola pín sí méjì àwọn ni ìlú yola àtijó níbi tí lamido ìlú náà gbé àti ìlú jimeta ìlú jimeta ní àárín ètò ọ̀rọ̀ ajé yola
yola nigeria <ns>0</ns> <revision> <timestamp>2008-02-18t184319z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> </contributor> <comment>yola nigeria moved to yola</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format>
eṣinṣin àwọn eṣinṣin jẹ́ kòkòrò ninu ito awon oníyẹ̀ẹ́meji diptera lati ede griiki di = meji ati ptera = iye iyato won kedere si awon kokoro miran ni esinsin ni iye ifo meji ni aya-arin ati pair of haltere meji to wa lati iye eyin ni aya-ikeyin awon irueda esinsin kan yato nitoripe won ko le fo awon kokoro miran ti won...
ẹṣin ẹsin the horse equus ferus caballus is a domesticated odd-toed hoofed mammal it belongs to the taxonomic family equidae and is one of two extant subspecies of equus ferus the horse has evolved over the past 45 to 55 million years from a small multi-toed creature eohippus into the large single-toed animal of today ...
uyo uyo ni olú-ìlú ìpínlẹ̀ akwa ibom ní guusu nàìjíríà ibibio ni èdè tí wón sọ ní ìlú uyo uyo di olú-ìlú ìpínlẹ̀ akwa ibom ní ọjọ́ ketalelogun oṣù kẹsànsept 23 ọdún 1987 nígbà tí akwa ibom yapa kúrò lára ìpínlẹ̀ cross river gẹ́gẹ́ bi àbájáde ètò ìkànìyàn nàìjíríà ọdún 2006 iye àwọn ènìyàn tí ó ń gbé uyo àti ní ìlú itu ...
òṣogbo òṣogbo jẹ́ ìlú ńlá kan ní ìpílẹ̀ ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà bákan náà ni ó jẹ́ olú ìlú fún ìpínlẹ̀ náà ní apá ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ nàìjíríà ọ̀gbẹ́ni gbóyèga òyètọ́lá ni gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun lọ́wọ́lọ́wọ́ òṣogbo di olú ìlú fụ́n ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun ní ọdun 1991 bákan náà ni ó tún jẹ́ olú ilé-iṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ fún ìlú òṣogbo...
paul kagame <ns>0</ns> <revision> <parentid>524146</parentid> <timestamp>2019-11-06t114500z</timestamp> <contributor> <ip>2121570218</ip> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> paul kagame ojoibi 23 october 1957 lowolowo ni aare orile-ede olominira ile ruwanda ikefa
rwanda orile-ede olominira ile rwanda je orile-ede ni apa ilaoorun afrika
kigali kigali je oluilu orile-ede rwanda
bùrúndì bùrúndì pipe lonibise bi orílẹ̀-èdè olómìnira ilẹ̀ bùrúndì buˈɾundi je orile-ede ademolesarin ni agbegbe awon adagun ninla ni apailaorun afrika to ni bode mo rwanda ni ariwa tanzania ni ilaorun ati guusu ati orile-ede olominira oloselu ile kongo ni iwoorun oluilu re ni bujumbura botilejepe orile-ede na je ademo...
wole soyinka
ebun nobel
samuel akintola <ns>0</ns> <revision> <parentid>411621</parentid> <timestamp>2013-02-11t181756z</timestamp> <contributor> <username>xqbot</username> </contributor> <minor /> <comment>robot fixing double redirect to samuel ladoke akintola</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format>
ladoke akintola
action group ẹgbẹ́ ìṣèlú action group jẹ́ ìkan nínú àwọn lààmì-laaka ẹgbẹ́ òṣèlú ajìjà òmìnira fún orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ìlú ìbàdàn n inú oṣù kẹta ọdún 1951 láti ọwọ́ alagba ọbáfẹ́mi awólọ́wọ̀ ìdí tí wọ́n fi dá ẹgbẹ́ yí sílẹ̀ ni láti rú ìmọ̀sílára àwọn ọmọ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà láti gbé ìgbésẹ̀ àti ...
greesi
yúrópù
islàm
ìjọba ìbílẹ̀ bẹ́núé benue benue ado agatu apa buruku gboko guma gwer east gwer west katsina ala konshisha kwande logo makurdi obi ogbadibo ohimini oju okpokwu otukpo tarka ukum ushongo vandeikya
chima nwafor chima nwafor alaisi 25 march 2005 je oloselu omo ile naijiria ati igbakeji gomina ipinle abia si orji kalu o ku ni march 21 2005 won si sin in ni september 2 2006 ni ulu re ni umuojima ni ipinle anambra ko pe ti won yo o kuro ni ori oye ti o fi ku won se isn idagbere fun un ni st clement's anglican church ...
za za je ti orile-ede guusu afrika
ìpínlè oyo <ns>0</ns> <revision> <parentid>20277</parentid> <timestamp>2008-08-30t195729z</timestamp> <contributor> <username>redirect fixer</username> </contributor> <comment>ipinle oyo has been moved it is now a redirect to ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format>
adebayo alao-akala christopher adébáyọ̀ àlàó akálà ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹ́ta oṣù kẹfà ọdún 1950 ó sì kú ní ọjọ́ kejìlá oṣù kínní ọdún 2022 1950 - 2022 christopher adébáyọ̀ àlàó akálà jẹ́ olóṣèlú àti gómìnà nígbà kan rí ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 2019 ó díje dupò gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ lẹ́ẹ̀kan si lábẹ́ ...
christopher adebayo alao-akala
christopher alao-akala
ipinle lagos
theodore orji theodore ahamefule orji ni wọ́n bí ní 11/11/1950 ó jẹ́ olóṣèlú ará ilẹ̀ nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ abia láti ọdún 2007 títí dé 2015 ní ìgbàkan rí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba àti pé ó jẹ́ olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ní abẹ́ gómìnà orji uzor kalu ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú pdp lọ́wọ́lọ́wọ́
robert menzies robert gordon menzies je oloselu omo ile australia ni menzies a bi i ni 1894 o je olootu ijoba ile australia fun odun mokandinlogun ilu jepart ni won ti bi i ni victoria o gba oye ninu ofin ni university melborne ni aarin 1928 si 1934 o wa ni victoria state legislature nigba ti o se o wo federal house of...
olusegun agagu olusegun kokumo agagu born 16 february 1948 je oloselu omo ile naijiria ati gomina ipinle ondo lati 29 may 2003 titi di 23 february 2009 nigbati ile-ejo alatunejoda ni ilu benin fagile idiboyan april 2007 nitori pe ko bo fin mu wọ́n bí i ní ferbruary 16 1948 ní òkìtìpupa ondo state ó bẹ̀rẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ ní ...
ìpínlẹ̀ mississippi <ns>0</ns> <revision> <parentid>516552</parentid> <timestamp>2023-09-25t091853z</timestamp> <contributor> <username>internetarchivebot</username> </contributor> <comment>rescuing 1 sources and tagging 0 as dead #iabot v2095</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> mississippi i...
ìpínlẹ̀ missouri missouri je ipinle kan ni ile amerika aarin gbungbun iwo-oorun ile amerika ni ipinle yii wa oke kan ti o n je ozark mountain wa nibe ibe naa ni omi kan ti o n je missouri wa apapo omi missouri yii ati mississippi ni odo ti o gun ju ni agbaye ile-ise po ni ipinle tii awon eniyan ti o n gbe ibe to 466700...
mojave desert asale mojave california ni asale yii wa ni iwo-oorun amerika awon nnkan ti o wa ni asale yii ni yanrin okuta volcanic rock ati awon adagun odo lake ti o ti gbe o fe to 15000 square mile loooto won ko le dako ni mojave desert won maa n ri awon ohun alumo-onni ile bii goolu silifa ati tungsten ni ibe
afríkà
de de je ti ile jẹ́mánì
odun todogba <ns>0</ns> <revision> <timestamp>2008-02-24t014840z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> </contributor> <comment>redirecting to ọdún tódọ́gba</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format>
apa ilaoorun afrika
kofi annan kofi atta annan 8 april 1938 - 18 august 2018 je omo orile-ede ghana to je diplomati to wa ni ipo gege bi akowe agba keje agbajo iparapo awon orile-ede lati 1 january 1997 de 31 december 2006 annan ati agbajo iparapo awon orile-ede jo gba ebun nobel fun alafia ni 2001
iposieniyan
blu-ray disc blu-ray disc blu-ray tabi bd je akaaba olojuina-ribiti amounmaworan optical-disc media storage
walter raleigh <ns>0</ns> <revision> <parentid>414255</parentid> <timestamp>2013-03-08t024411z</timestamp> <contributor> <username>addbot</username> </contributor> <minor /> <comment> migrating 40 interwiki links now provided by on </comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> walter raleigh a bi i ni...
eku eku orisii meji lo wa dudu ati pupa resuresu brown awon eku maa n gun ni iwon insi merindinlogun ninu eyi ti insi mejo re maa n je iru won maa n ba nnkan je pupo ni pataki awon ti o dudu ni laboretiri won maa n sin awon eku funfun kan ti won fi maa n se iwadii
mẹ́ksíkò àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́síkò aṣọ̀kan estados unidos mexicanos lédè sípéènì tàbí mẹ́síkò ní ṣókí jẹ́ orílẹ̀-èdè ní apá àríwá amẹ́ríkà èdè sípéènì ni wọ́n ń sọ níbẹ̀ apá gúúsù orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ló wà àwọn ọmọ sípéènì ṣẹ́gun mẹ́síkò lọ́dún 1519 ọ̀pọ̀ àwọn mestizo wà nínú àwọn ènìyàn tó wà ní mẹ́síkò ìyẹn ni àwọn tí òbí...
michigan michigan je okan ninu awon ipinle ti o loro ju ni ile amerika ni michigan o fi egbe ti canada ati awon great lakes maraarun awon eniyan to n gbe ibe to 8 875000 won n se kaa pupo ni ipinle yii nitori pe won ni irin detroit je okan lara awon ilu pataki ti won ti n se kaa ni michigan awon ara ile faranse ni o ko...
ye ye ni amioro orile-ede top-level domain cctld ori internet fun yemen
wf wf je ti wallis and futuna islands
vu vu
vn vn