raw_text
stringlengths
2
128k
àríwá amẹ́ríkà àríwá amẹ́ríkà
ọ̀rànmíyàn nínú ìtàn àròsọ/àtẹnudẹ́nu ilẹ̀ yorùbá ọ̀rànmíyan tàbí ọ̀rányàn jẹ́ ọba láti ilé-ifẹ̀ bẹ́ẹ̀ ni ó tún jẹ́ ọmọ odùduwà ohun ni ìtàn àròsọ ẹnu yí sọ wípé ó dá ìlú ọ̀yọ́ sílẹ̀
mọ̀nàmọ́ná mọ̀námọ́ná je itusile agbara isele ina larin ayika afefe isele ina yi lo n fa àgbàrá òjò àrá wa
2001 <ns>10</ns> <id>10717</id> <revision> <id>160243</id> <parentid>157824</parentid> <timestamp>2011-01-04t164512z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> ọ̀rúndún | ọ̀rúndún 210k ◄◄ | | | 2001 odun 2001
ilu ọyẹ́ yemitan yoruba oral literature poetry ijala literature ọladipọ yemitan ijala aré ọdẹ itan ilu oye ati igbeti oye igbeti itan ilu ọyẹ́ ati ìgbẹ́tì ojú-ìwé 39-41 alaye ọyẹ́ ati ígbẹ́tì jẹ meji ninu awọn ilu ilẹ yoruba itan bi nwọn ti ṣe dá ilu mejèji yi silẹ ni a sọ ninu ijalá yi ilu ọyẹ́ tit u tipẹ ṣugbọn ìgbẹ́...
ọ̀fà ìlú ọ̀ffà jẹ́ ìlú kan ní ìpínlẹ̀ kwara ní apá iwọ̀-oòrùn ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ọ̀ffà ni adásílẹ́ nípasẹ̀ olálómi ọlọ́fà-gangan ọmọ-aládé adé láti ọ̀yọ́ àti irú-ọmọ tààrà tí ọba ọ̀rànmíyàn ní ilé-ifè ní bí ọdún1395 ó jẹ́ ọdẹ olókìkí tafàtafà ọ̀ffà ni olú-ìlú ìbílè ti èdè abínibí ti ìbòlò ti àwọn ènìyàn tí ó ńsọ èd...
boris yeltsin bọris nìkòláyefìts yẹ́ltsìn rọ́síà 1 february 1931 23 april 2007 ni o je ààrẹ àkọ́kọ́ ile rọ́síà
adebayo adefarati adebáyò adéfaratì february 14 1931 march 29 2007 je oloselu ara orile-ede naijiria ati gómínà ìpínlẹ̀ òndó tele adefarati kú ní ojokandinlogbòn osù kéta odún 2007
ryszard kapuscinski ryszard kapuściński je omo ilẹ̀ polandi tí ó jẹ́ òǹkọ̀wé àti oníròyìn kú ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kìíní ọdún 2007
cristina fernández de kirchner cristina elisabet fernández de kirchner born 19 february 1953 sometimes referred to by her initials cfk je oloselu ati agbejoro ara argentina ati aare ile argentina tele òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí wọn yóò dìbò yàn gẹ́gẹ́ bí olórí ìjọba president ní ilẹ̀ argentina ọwọ́ ọkọ rẹ̀ president nes...
memphis 'memphis je ilu kan ni ipinle tennessee ni ile amerika
ìjíptì ìjíptì tabi orilẹ-èdè olómìínìra arabù ilẹ ìjíptì je orile-ede ni ariwa afrika
ìjẹ̀bú ìjẹ̀bú jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà èdè yorùbá ó ṣòro láti sọ pàtó ìgbà tí a dá ìlú ìjẹ̀bú sílẹ̀ nítorí pé àwọn àgbà tí a fi ọ̀rọ̀ wá lẹ́nu wò wọ́n kò mọ̀-ọ́n-kọ tàbí mọ̀-ọ́n-kà ṣùgbọ́n wọ́n sọ wí pé “ajẹbú” ni orúkọ ẹni tí ó dá ìlú ìjẹ̀bú sílẹ̀ ń jẹ́ ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ìjẹ̀bú ajẹbú àti olóde jẹ́ ọdẹ gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti s...
hausa hausa le toka si
ìṣọ̀kan áfríkà ìṣọ̀kan áfríkà gígékúrú bí au ní èdè gẹ̀ẹ́sì tàbí ua jẹ́ ẹgbẹ́ ìṣọ̀kan tó ní àwọn orílẹ̀-èdè olómìnira adúláwọ̀ márùnléláàádọ́ta 55 bí ọmọ ẹgbẹ́morocco nìkan ni orílẹ̀-èdè olómìnira tí kìí ṣe ọmọ ẹgbẹ́ àjọ ìṣọ̀kan adúláwọ̀ ìṣọ̀kan afrikà jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọjọ́ kẹsàn án oṣù keje ọdún 2002 9-7-2002 àjọ au n...
olúbàdàn olubadan ni oruko oye oba ilu ibadan olubadan to wa lori oye lowolowo bayii ni 2016 ni sálíù adétúnjí
ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ìpínlẹ̀ oyo jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì tí ó wà ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìpínlẹ̀ yí wà ní ìwọ̀ oòrùn orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí olú ìlú rẹ̀ sì fìdí kalẹ̀ sí ìlú ìbàdàn tí olú ìlú rẹ̀ sí jẹ́ ìlú kẹta tí ó lérò púpò julọ ni orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí o si figbakan je ìlú kejì tó lérò púpò julọ ní áfrí...
ìpínlẹ̀ adamawa ìpínlẹ̀ adamawa fula leydi adamaawa 𞤤𞤫𞤴𞤣𞤭 𞤢𞤣𞤢𞤥𞤢𞥄𞤱𞤢 jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní agbègbè àríwá-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó pín ààlà pẹ̀lú ìpínlẹ̀ sí àríwá ìwọ̀-oòrùn sí ìwọ̀-oòrùn àti gúúsù-ìwọ̀-oòrùn nígbàtí ààlà ìlà-oòrùn rẹ̀ di apákan ààlà orílẹ̀ èdè pẹ̀lú orílẹ̀ èdè orúkọ rẹ̀ jẹ yọ látara ì...
ìpínlẹ̀ akwa ibom ìpínlẹ̀ akwa ibom jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní agbègbè ẹkù-ìjọba gúúsù-gúúsù orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó pín ààlà ní ìlà-oòrùn pẹ̀lú ìpínlẹ̀ ní ìwọ̀-oòrùnon ìpínlẹ̀ àti ìpínlẹ̀ àti ní gúúsù pẹ̀lú ìpínlẹ̀ náà mú orúkọ rẹ̀ látara orúkọ odò tí ó pín ìpínlẹ̀ náà sí ọgbọọgba kí ó tó sàn wọ inú ìpínlẹ̀ akwa ibom yapa wá...
ìpínlẹ̀ anambra ìpínlẹ̀ anambra jẹ́ ìpínlẹ̀ kan láàárín àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà ní agbègbè gúúsù-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè náà wọ́n dá ìpínlẹ̀ náà lẹ̀ ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n ọdún 1991 ìpínlẹ̀ anambra sopọ ìpínlẹ̀ delta sí ìwọ̀-oòrùn ìpínlẹ̀ sí gúúsù ìpínlẹ̀ sí ìlà-oòrùn ̀ti ìpínlẹ̀ sí àríwá gẹ́gẹ́ ...
ìpínlẹ̀ bauchi ìpínlẹ̀ bauchifula leydi bauchi 𞤤𞤫𞤴𞤣𞤭 𞤦𞤢𞤵𞤷𞥅𞤭 jẹ́ ìpínlẹ̀ kan láàárín àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ní agbègbè àríwá-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó pín ààlà pẹ̀lú ìpínlẹ̀ àti si àríwá pẹ̀lú ìpínlẹ̀ àti sí gúúsù pẹ̀lú ìpínlẹ̀ àti sí ìlà-oòrùn àti pẹ̀lú ìpínlẹ̀ sí ìwọ̀-oòrùn ó mu orúkọ rẹ̀ lát...
wikipedia wikipedia jé isé owó òpòlopò àwon ènìyàn kâkiríayé láti se ìwé ìmò tó jé òfé ni òpòlopò èdè ni òrí internet ti wikimedia foundation n se onigbowo wikipedia a ma ran ènìyàn pupo lowo l'òpòlopò
ìpínlẹ̀ bayelsa ìpínlẹ̀ bayelsa jẹ́ ìpínlẹ̀ kan láàárín àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ní agbègbè gúúsù-gúúsù ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó wà ní gbùnnùgbúnnù agbègbè wọ́n dá ìpínlẹ̀ sílẹ̀ ní ọdún 1996 wọ́n sì dá ààyè rẹ̀ yọ kúrò nínú ìpínlẹ̀ ní èyí tí ó mu jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìpínlẹ̀ titun ní orílẹ̀ èdè ni olú-ìlú rẹ̀ ìpí...
ìpínlẹ̀ bẹ́núé <ns>0</ns> <revision> <parentid>550427</parentid> <timestamp>2022-09-27t153230z</timestamp> <contributor> <username>enitanade</username> </contributor> <comment>atunkọ arokọ</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> ìpínlẹ̀ benue jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní agbègbè àríwá àáríngbùn...
ìpínlẹ̀ borno ìpínlẹ̀ borno jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní agbègbè àríwá-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó pín ààlà pẹ̀lú ìpínlẹ̀ sí ìlà-oòrùn ìpínlẹ̀ sí gúúsù-ìlà-oòrùn àti ìpínlẹ̀ sí gúúsù nígbà tí ó àwọn ààlà ìlà-oòrùn rẹ̀ parapọ̀ di ààlà orílẹ̀ èdè pẹ̀lú orílẹ̀ èdè ààlà àríwá rẹ̀ parapọ̀ di ààlà orílẹ̀ èdè pẹ̀lú orílẹ̀ èdè àt...
ìpínlẹ̀ abia ìpínlẹ̀ abia jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní agbègbè gúúsù-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó pín ààlà sí àríwá àti àríwá-ìlà-oòrùn pẹ̀lú àwọn ìpínlẹ̀ àti sí ìwọ̀-oòrùn ìpínlẹ̀ sí ìlà-oòrùn ìpínlẹ̀ sí gúúsù-ìlà-oòrùn àti ní ìpínlẹ̀ sí gúúsù tí wọ́n sọ lórúkọ látara ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ orúkọ àwọn agbègbè mẹ́rin tí ó pọ̀ jùlọ ní ì...
ìpínlẹ̀ cross river ìpínlẹ̀ cross river jẹ́ kan láàárín àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ní agbègbè ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà wọ́n sọọ́ lórúkọ fún àwọn ará wọ́n dá ìpínlẹ̀ náà sílẹ̀ látara ìlà-oòrùn ní agbègbè ìlà-oòrùn ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún1967 olú-ìlú rẹ̀ ni ó pín ààlà sí àríwá pẹ̀lú ìpínlẹ̀ sí ìwọ̀-oòrù...
ìpínlẹ̀ delta ipinle delta je ipinle kan nini awon ipinle ni orile-ede naijiria ìpínlè delta wà ní apa guusu nàìjíríà adá ìpínlè delta kalè ní ojo ketadinlogbon osu kejo odun 199127 august 1991 ní abe isejoba gen ibrahim babangida olú-ìlú ìpínlè delta ní asaba bí otile jepe ìlú warri ìkan aje/oja kale sí jù àwon èyà tí...
ìpínlẹ̀ ebonyi ìpínlẹ̀ ebonyi jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní agbègbè gúúsù-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó pín ààlà sí àríwá àti àríwá-ìlà-oòrùn pẹ̀lú ìpínlẹ̀ ìpínlẹ̀ sí ìwọ̀-oòrùn ìpínlẹ̀ sí ìlà-oòrùn àti gúúsù-ìlà-oòrùn àti ìpínlẹ̀ sí gúúsù-ìlà-oòrùn wọ́n fún un orúkọ fún àwọn ará —apá kan tó gbòòrò ní ẹkù gúúsù ìpínlẹ̀ náà—w...
ìpínlẹ̀ edo ìpínlẹ̀ edo jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó wà ní agbègbè ẹkù gúúsù ti orílẹ̀ èdè náà gẹ́gẹ́ bí àbájáde ètò-ìkànìyàn lórílẹ̀ èdè ti ọdún 2006 ìpínlẹ̀ náà jẹ́ ìpínlẹ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹrìndínlọ́gbọ̀n ní iye pẹ̀lú ènìyàn tí ó tó mílíọ́nnù mẹ́ta-àbọ̀-dínní-díẹ̀ ní orílẹ̀ èdè nàìjí...
agbègbè olú-ìlú ìjọba àpapọ̀ nàíjíríà
ìpínlẹ̀ èkìtì ìpínlẹ̀ èkìtì jẹ́ ìpínlè ní apá ìwọ̀ oòrùn nàíjíríà tí ó jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọjọ́ kìíní oṣù ọwàwà1996 pẹ̀lú àwọn ìpínlẹ̀ tuntun márùn-rún mìíràn látọwọ́ ọ̀gágun sani abacha èkìtì ti jẹ́ ìpínlẹ̀ olómìnira kí àwọn òyìnbó tó dé èkìtì jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìpílẹ̀ yorùbá ní ibi tí a mọ̀ sí orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní òn...
ìpínlẹ̀ enugu ìpínlẹ̀ enugu igbo ȯra enugu jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní agbègbè gúúsù-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó pín ààlà sí àríwá pẹ̀lú ìpínlẹ̀ benue àti ìpínlẹ̀ kogi ìpínlẹ̀ ebonyi sí ìlà-oòrùn àti gúúsù-ìlà-oòrùn pínlẹ̀ abia sí gúúsù àti ìpínlẹ̀ anambra sí ìwọ̀-oòrùn ìpínlẹ̀ náà gba orúkọ rẹ̀ látara olú-ìlú rẹ̀ àti ìl...
ìpínlẹ̀ gombe ìpínlẹ̀ gombe jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní agbègbè orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó pín ààlà sí àríwá àti àríwá-ìlà-oòrùn pẹ̀lú ìpínlẹ̀ àti ìpínlẹ̀ sí gúúsù pẹ̀lú ìpínlẹ̀ sí gúúsù-ìlà-oòrùn pẹ̀lú ìpínlẹ̀ àti sí ìwọ̀-oòrùn pẹ̀lú ìpínlẹ̀ wọ́n sọọ́ lórúkọ fún ìlu —tí ó jẹ́ olú-ìlú ìpínlẹ̀ àti ìlú tí ó gbòòrò jùlọ—wọ́n ṣẹ̀da ì...
ìpínlẹ̀ imo ìpínlẹ̀ imo jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní agbègbè gúúsù-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó pín ààlà sí àríwá pẹ̀lú ìpínlẹ ìpínlẹ̀ sí ìwọ̀-oòrùn àti gúúsù àti ìpínlẹ̀ sí ìlà-oòrùn ó mú orukọ rẹ látara odò tí ó ń sàn jákèjádò ààlà ìlà-oòrùn olú-ìlú ìpínlẹ̀ náà ni tí orúkọ ìnagigẹ rẹ̀ ń jẹ́ ọkàn ìlà-oòrùn eastern heartla...
ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìpínlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun jẹ́ ìpínlẹ̀ tí ó wà ní àárín gbùngbùn apá ìwọ̀-oòrùn gúúsù orílẹ̀-èdè nàìjíríà olú-ìlú rẹ̀ wà ní ìlú òṣogbo ó ní ibodè ní àríwá mọ́ ipinle kwara ní ìlà-oòrùn díẹ̀ mọ́ ipinle ekiti àti díẹ̀ mọ́ ipinle ondo ní gúúsù mọ́ ipinle og...
ìpínlẹ̀ òndó state of nigeriaìpínlẹ̀ jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní gúúsù-ìwọ̀oòrùn orílẹ̀ èdè wọ́n da sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹ́ta oṣù kejí ọdún 1976 látara àwọn ìpínlẹ̀ ìwọ̀ oòrùn tẹ́lẹ̀ rí pín ààlà pẹ̀lú ìpínlẹ̀ sí pẹ̀lú ìpínlẹ̀ sí àríwá-ìlà-oòrùn pẹ̀lú ìpínlẹ̀ sí ìlà-oòrùn pẹ̀lú ìpínlẹ̀ sí gúúsù-ìlà-oòrùn pẹ̀lú ìpínlẹ̀ sí gúúsù-ìwọ̀ oò...
ìpínlẹ̀ ògùn state of nigeria ìpínlẹ̀ ògùn jẹ ọ̀kan lára àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì tí ó wà ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n da ìpínlẹ̀ ògùn sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kejì ọdún 1976 ìpínlẹ̀ ògùn fi ẹ̀gbẹ́ kan ẹ̀gbẹ́ pẹ̀lú ìpínlẹ̀ èkó lápá gúúsù ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ àti ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun lápá àríwá ìpínlẹ̀ òndó àti orílẹ̀-èdè olómìnir...
ìpínlẹ̀ èkó ìpínlẹ̀ èkó jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní gúúsù ìwọ̀-oòrùn láàárin àwọn ìpńilẹ̀ mẹ́rìndìnlógójì náà ó pọ̀ níye ó sì kéré ní ààyè ó sopọ̀ mọ́ gúúsù nípasẹ̀ àwọn àti sí ìwọ̀-oòrùn nípasẹ̀ ààlà òkèèrè pẹ̀lu ìpínlẹ̀ èkó ń pín àwọn ààlà pẹ̀lú ìpínlẹ̀ ogun sí ìlà-oòrùn àti àríwá ní èyí tí ó mu jé ìpńilẹ̀ kan ṣoṣo ní orílẹ̀-...
ìpínlẹ̀ rivers <ns>0</ns> <revision> <parentid>579357</parentid> <timestamp>2023-12-21t074412z</timestamp> <contributor> <username>internetarchivebot</username> </contributor> <comment>rescuing 1 sources and tagging 0 as dead #iabot v2095</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> ìpínlẹ̀ ní nàìjírí...
idi amin dada idi amin dada c1925a 16 august 2003 je oga ologun ati aare orile-ede uganda lati 1971 de 1979
ewì ajẹmókùú songs ìlò orin yorùbá jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà tó fẹ́ràn orin púpọ̀ kò sí abala kan nínú ìgbésí ayé ọmọnìyàn tí a kò ti lè kọrin a ń kọ orin níbi ìgbeyàwó à ń kọ orin nígbà tí a bá bímọ nígbà ìsìnkú àgbà orin wà láti yin olódùmarè bẹ́ẹ̀ ni orin wà láti fi àseyọrí tàbí kù dìẹ̀ ku diẹ ẹ̀dá hàn gbogbo ìwà àti...
uganda uganda yuganda ni awọn ede ugandan ti ijọba olominira ti uganda swahili jamhuri ya uganda jẹ orilẹ-ede ti ko ni ilẹ ni ila-oorun afirika orilẹ-ede naa ni bode si ila-oorun nipasẹ kenya si ariwa nipasẹ south sudan si iwọ-oorun nipasẹ democratic republic of congo si guusu-iwọ-oorun nipasẹ rwanda ati si guusu nipas...
ìpínlẹ̀ kwara kwara jẹ ìpínlẹ̀ ní apá ìwọ̀-oòrùn ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà olú-ìlú rẹ̀ ni ìlọrin ó wà ní àríwá àárín gbùngbùn ti a mò sí ìgbánú àárín ìlú yorùbá pèlú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn nupe ìbàrìbá àti fúlàní díẹ̀ ni wọ́n tẹ̀dó síbẹ ìpínlè kwárà ní ìjoba ìbílẹ̀ mérìndilógún ìjoba ìpínlè ti ìwò oòrùn ìlorin ni ènìyàn tó pòjù ...
ìpínlẹ̀ kogí ìpínlẹ̀ kogí jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó pín ààlà sí ìlà-oòrùn pẹ̀lú àwọn ìpínlẹ̀ àti sí àríwá ní agbègbè olú-ìlú sí àríwá-ìlà-oòrùn pẹ̀lú ìpínlẹ̀ sí àríwá-ìwọ̀ oòrùn pẹ̀lú ìpínlẹ̀ sí gúúsù-ìwọ̀ oòrùn pẹ̀lú àwọn ìpínlẹ̀ àti sí gúúsù-ìlà-oòrùn pẹ̀lú àwọn ìpínlẹ̀ àti àti sí ìwọ̀ oòrùn pẹ̀lú ì...
ìpínlẹ̀ plateau state of nigeria ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa àwọn ìpínlẹ̀ orílẹ̀-èdè nàìjíríà fún àti àwọn míràn ẹ wo plateau disambiguation ìpínlẹ̀ plateau jẹ́ ìpínlẹ̀ ìkejìlá tí ó wà ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó tòní jùlọ ìpínlẹ̀ yí wà ní àárín gbùngbùn orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí àwọn òkè àpáta orísiríṣi sì yi ka pàá pàá jùlọ ...
ìpínlẹ̀ kaduna ìpínlẹ̀ kàdúná jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìdínlógójì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìpínlẹ̀ kàdúná jẹ́ ọkan lára ìpínlẹ̀ tó wà ní apá àríwá orílẹ̀-èdè nàìjíríà olú-ìlú ìpínlẹ̀ yìí ń bá a jórúkọ ìlú kàdúná èyí tí ó jẹ́ ìlú kẹ́jọ tí ó tóbi jù ní orílẹ̀-èdè yìí ní ọdún 2006 wọ́n dá ìpínlẹ̀ yìí sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ...
ìpínlẹ̀ jigawa ìpínlẹ̀ jigawa jẹ́ ọkan nínu ìpínlè mẹ́rìndínlógójì orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìpínlẹ̀ yí wà ní apá àríwá orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọdún 1991 láti apá ìwọ̀ oòrùn gúsù kánò jigawa wa ni ààlà tó wà lárin orílẹ̀-èdè niger ati orílẹ̀-èdè nàìjíríà dutse ni olú ìlú fún ìpínlẹ̀ náà tí ósìjẹ́ ìlú tí o tóbi...
àdìsá akinloyè augustus meredith àdìsá akinloyè august 19 1916 september 18 2007 jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ naijiria
adisa akinloye
ìpínlẹ̀ niger state of nigeria ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa a state in nigeria fún the sovereign country of the same name ẹ wo niger niger jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ààrin gbùngbùn apá àríwá lórílẹ̀-èdè nigeria ó jẹ́ ìpínlẹ̀ tó tóbi jù lọ ní nàìjíríà wọ́n pín ìpínlẹ̀ niger sí àgbègbè-ìṣèjọba mẹ́ta ní ìpín a b d minna ni olú-ìlú ìpínlẹ̀...
ìpínlẹ̀ nasarawa ìpínlẹ̀ násáráwá je ikan ninu àwon ipinle 36 ni orile-ede naijiria oluilu re ni lafia ítàn ìdásílẹ̀ ìpínlẹ̀ nasarawa jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọjó kínní osù kẹwàá ọdún 1996 nígbà ìsèjọba abacha tí wọ́n pín kúrò ní ìpínlẹ̀ plateau odè oní ijọba ìbílẹ̀ awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ nasarawa jẹ́ mẹ́tàlá afì...
ipinle kano ìpínlẹ̀ kánò jẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ kánò àti ìlú tí ó tóbijùlo ẹ̀kẹta ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà lẹ́yìn ìlú ìbàdàn àti ìlú èkó gẹ́gẹ́ bí ìkànìyàn ọdún 2006 kano jẹ́ ìpínlẹ̀ tí ó ní èrò jùlọ ní orílẹ̀̀ èdè nàìjíríà àwọn ibi tó lajú níbẹ̀ gba ìlẹ̀ tó tóbi tó 137 km2 tí ó sì ní àwọn ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́fà — kano municipa...
lucky dube lucky dube omo ile south africa ni lucky dube orin reggae ni lucky dube maan ko nigba aye re lucky dube olórin reggae ní south africa kú ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹ́wàá ọdún 2007
ìpínlẹ̀ kebbi state of nigeria kebbi túndarí síbí yìí fún òmíràn ẹ wo kebbi ìṣojútùú ìpínlẹ̀ kébí tí ìfohùnpè rẹ̀ lèdè hausa àti àwọn èxè míràn ń jẹ́ fulfulde leydi kebbi 𞤤𞤫𞤴𞤣𞤭 𞤳𞤫𞤦𞥆𞤭 jẹ́ ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ tí ó wà ní apá òkè ọya àti ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì tí wọ́n wà ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ...
karl marx karl heinrich marx may 5 1818 march 14 1883 je ara jemani amoye aseoro-okowo oloselu akoitan aserojinle oloselu aseoro-awujo ati asekomunisti alajidide ti awon irookan re ko ipa pataki ninu idagbasoke isekomunisti ati isesosialisti odeoni marx se soki ohun to unso niu ila akoko ori kinni iwe re manifesto komu...
peter abelard peter abelard a bí i ní 1079 ó kú ní 1142 ó jé òkan lára àwon tí ó sèdá ohun tí a n pè ní scholastic theology olùkó ni ní paris òpò akékòó ni ó máa n wá sódò rè òpin ìfé láàrin òun àti heliose kò dára
ìtàn ìsèdálẹ̀ ilé-ifẹ̀ ìlú ilé-ifẹ̀ jẹ́ ìlú tí òrìṣà bàbá ṣìgìdì tí mo fẹ́ sọ ìtàn rẹ̀ ti wá èyí ló mú mi yà bàrá láti sọ ní ṣókí nípa ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ìlú ilé-ifẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ ló ti wà lórí ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ìlú ilè-ifẹ̀ bẹ́ẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ àwọn òǹkọ̀wé àti òǹpìtàn ló ti fi èrò wọn hàn lórí ìtan ìṣẹ̀dálẹ̀ ìlú ilé-ifẹ̀ ọ̀jọ...
ọ̀nà tí a lè pín òrìṣà ilẹ̀ yorùbá sí ọ̀nà tí a lè pín àwọn òrìṣà ilẹ̀ yorùbá sí ẹnu kò kò lórí iye àwọn òrìṣà tó wà nílẹ̀ yorùbá bí àwọn kan se sọ pé ọ̀kànlénígba òrìṣà ló wà ní aàfin ọ̀ọ̀ni bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn kan ń sọ pé irinwó òrìṣà ó lẹ́ ọ̀kan 401 deities ló wà lóde ìṣálayé à ò lè sọ pàtó iye òrìṣà ilẹ̀ yorùbá tó wà...
amẹ́ríkà látìnì ìfáàrà “ẹ tọ́kọ́ máa wa ìjọba òsèlú ná èyí tókù a ó sì fi fún yin àpilẹ̀kọ yìí ṣe àgbéyẹ̀wò ìbásepọ̀ láàrin afíríkà yorùbá àti ètò ìsèjọba ni latin america àti ní pàtàkì jùlọ bi wọn se igbógun tí àwọn ènìyàn afíríkà nípa kíkópa nínú ìsèjọ̀ba latin amẹrika nígbà tí brazil yóò dúró gẹ́gẹ́ bii burè fún sís...
mohandas karamchand gandhi mohandas karamchand gandhi ojo ibi 2 october 1869 - 30 january 1948 je omo ile india
índíà índíà tàbí orílẹ̀-èdè olómìnira ilẹ̀ índíà ní èdè híńdì भारत गणराज्य bhārat gaṇarājya jẹ́ orílẹ̀-èdè kan ní gúúsù éṣíà ohun ni orílẹ̀-èdè kejè títóbi júlọ̀ gẹ́gẹ́ bí ìtóbí jẹ́ọ́gráfì orílẹ̀-èdè kìn-ín-ni tó ní ìye àwọn ènìyàn júlọ pẹ̀lú bíi 143 bílíọ̀nù ènìyàn àti ìjọba-oníbò tó ni ìye àwọn ènìyàn júlọ̀ lágbàyé ó...
egbé osèlú olómìnira tí puèrtó ríko egbé osèlú olómìnira tí puèrtó ríko jẹ́ ègbé òsèlú ni orílè-èdè puerto rico
ìpínlẹ̀ sokoto ipinle sokoto jé ikan ninu awon ipinle mérìndilógún tí o wà ní orile-ede naijiria ìpínlè sokoto wà ní àríwá ìwọ̀ oòrùn nàìjíríà oruko gomina ipinle sokoto lowolowo bayii ni arakunrin tanbuwal ijọba ìbílẹ̀ awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ sokoto jẹ́ mẹ́tàlẹ́lógún awon na ni
ìpínlẹ̀ taraba state of nigeriataraba fula leydi taraba 𞤤𞤫𞤴𞤣𞤭 𞤼𞤢𞤪𞤢𞤦𞤢 jẹ́ ìpínlẹ̀ ní àríwá-ìlà-oòrùn tí wọ́n sọọ́ ní orúkọ ní ìbámu pẹ̀lú ní èyí tí ó sàn jákèjádò gúúsù ìpínlẹ̀ náà olú-ìlú ìpínlẹ̀ taraba ni púpọ̀ àwọn olùgbe rẹ̀ ni wurkum àti àwọn ẹ̀ya kona ti wọ́n gbilẹ julọ apá àríwá ìpínlẹ̀ náà nígbàtí cha...
ìpínlẹ̀ yobe ìpínlẹ̀ yòbè je okan ninu awon ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ni orile-ede naijiria ìpínlẹ̀ yóbè jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní agbègbè àríwá-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó pín ààlà pẹ̀lú ìpínlẹ̀ borno ìpínlẹ̀ yóbè jẹ́ ipínlẹ̀ awọn nnkan ọ̀ọ̀gbìn ọjó kẹ́tadinloogbọn osù kèjọ ọdún 1991 ni wón dá sílẹ̀ ara ìpìnlẹ̀ bòrnó ni...
ìpínlẹ̀ zamfara ìpínlẹ̀ zamfara je ikan ninu awon ipinle 36 ni orile-ede naijiria àwọn agbègbè ìjọba ìpínlẹ̀ zamfara ìpínlẹ́ zamfara ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́rínlá
ení
ọdún tódọ́gba ọdún tódọ́gba je odun kalenda to ni ọjọ́ kan le lati ba je ki odun kalenda o ni ibamu po mo igba odun
kí ni fíìmù fíìmù fíìmù jẹ́ ọ̀rọ̀ kàn tí a fi kó àwòràn papọ̀ a máa ń gbé fíìmù jáde nígbà tí a bá gbá àwòrán àwọn ènìyàn àti àwọn nǹkan sílẹ̀ pẹ̀lú kámẹ́rà tàbí tí a bá ṣẹ̀dá àwòràn nǹkan nípa lílo àwọn irinṣẹ́ kòmpútà a máa ń lo fíìmù láti ṣẹ̀fẹ̀ láti dá àwọn ènìyàn lára yá gẹ́gẹ́ bí irinṣẹ́ ńlá tí a fi ń kọ àwọn ará...
frederick douglass frederick douglass oruko abiso frederick augustus washington bailey february 1818 february 20 1895 je ara amerika alatunse alasodun olukowe ati babaalu leyin igba to sakuro ni oko-eru o di olori egbe irinkankan apokoerure pelu oro kankan re ati iwe alodi si oko-eru to ko ohun lo duro bi apere tolodi ...
29 february 28 february - 29 february - 1 march <ns>10</ns> <id>10812</id> <revision> <id>538182</id> <parentid>122275</parentid> <timestamp>2020-07-24t112709z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <minor /> <comment>dáàbò bòó àtúnṣe=gba àwọn alámùójútó nìkan láyè kòdájú ìyípò...
ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì tabi inglandi je orile-ede ara ìsọ̀kan ilẹ̀-ọba awon agbegbe ilegeesi list of regions east london south east south west east midlands west midlands yorkshire and<br>the humber north<br>east north west
ibrahim babangida ibrahim badamasi babangida ojoibi august 17 1941 je omo naijiria oga ologun to ti feyinti ogagun babangida fi igba kan je olori orile-ede naijiria lati odun 1985 titi de 1993 itokasi
ọdún ọdún kan jẹ́ iye àsìkó tí ó gba pílánẹ̀tì ilẹ̀-ayé làti fi yípo òòrùn kà lẹ́ẹ́kan péré ní fífàgùn a leè fi èyí múlẹ̀ fún pílánẹ̀tì yó wù bí àpẹẹrẹ ọdún máàsì kan yí ò jẹ́ àsìkò tí yí ò gba máàsì láti yípo òòrùn léèkan
ìkéde akáríayé fún àwọn ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn ìkéde káríayé fún è̟tó̟ o̟mo̟nìyàn ò̟rò̟ àkó̟so̟ bí ó ti jé̟ pé s̟ís̟e àkíyèsí iyì tó jé̟ àbímó̟ fún è̟dá àti ìdó̟gba è̟tó̟ t̟̟̟̟í kò s̟eé mú kúrò tí è̟dá kò̟ò̟kan ní ni òkúta ìpìlè̟ fún òmìnira ìdájó̟ òdodo àti àlàáfíà lágbàáyé bí ó ti jé̟ pé àìka àwo̟n è̟tó̟ o̟mo̟nìyàn sí àti ìk...
ábídí abidi
àbújá àbújá jẹ́ olú-ìlú fún orílé-èdè nàìjíríà ìlú yí ni ó jẹ́ àrin-gbùngbùn fún orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ilé ìjọba àpapọ̀ sì fìdí kalẹ̀ sí ní abẹ́ aso rock àpáta agbára ni àbújá àbújá dí olú-ìlú orílè-ede nàìjíríà ní osù kéjìlá odún 1991 àkọsílẹ̀ ètò ikaniyan ti ọdún 2006 sọ wípé àbújá ní olùgbé 776298
náírá currency of nigeriaowó náírà àmì ₦ àdàpè ngn ní owó tí wón ń lò fún títà-rírà ní nàìjíríà ọwọ́ náírà kan jẹ́ ọgọ́rùn-ún kọ́bọ̀ ilé-ìfowópamọ́ central bank ti nàìjíríà cbn nìkan ló láṣẹ láti ṣe owó síta ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìtàn nàìjíríà bẹ̀rẹ̀ sí ní lọ owó náírà ní ọjọ́ kìíní oṣù kìíní ọdún 1973 wọ́n pààrọ̀ owó...
euro euro ni oruko-owo egbe irepo europe ami owo euro je €
barack obama 44th american president barack hussein obama jr ojó-ìbí rẹ̀ ni ọjọ́ kẹrin oṣù kẹjọ ọdún 1961 jẹ́ olóṣèlú àti ààrẹ orílẹ̀-èdè ilẹ̀ amerika tele ó jẹ́ òloṣèlú orílẹ̀ èdè améríkà ọmọ ilé ìgbìmó aṣòfin láti ìpínlè illinois ọmọ ẹgbé òṣèlú democrat barack obama jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn òṣèlú méjì tí wón figagbága lát...
king sunny adé olóyè sunday adéníyì adégẹyè ọjọ́ọ̀bí- ọjọ́ kejìlélógún oṣù ọ̀wẹwẹ̀ ọdún 1946 tí a mọ̀ sí king sunny adé jẹ́ olórin jùjú ọmọ nàìjíríà òǹkọ̀tàn-orin àti onimọ̀-ọlọ́pọ̀ irinṣẹ́ ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olórin tàkasúfèé tí ó ṣe àṣeyọrí káríayé tí wọ́n sì tún mọ̀ ọ́ bí ọkàn lára àwọn olórin tó làmìlaka nígbà gb...
orin hip hop orin hip hop je eka orin odeoni
bob marley robert bob nesta marley 6 february 1945 11 may 1981 je olorin reggae omo ile jamaika
reggae reggae je eka orin ti o koko bere lati ile jamaika
unicef unicef ni ede geesi duro fun united nations children's fund ajo isokan awon orile-ede fun awon omode
ìwọ̀n ẹyọ akáríayé si ìwọ̀n ẹyọ akáríayé si ti a mo bi iwon si nisoki lati ede fransi to je le système international d'unités je ona iwon metriki </br>
ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ torile-ede áfríkà <ns>0</ns> <revision> <parentid>544455</parentid> <timestamp>2023-09-25t093017z</timestamp> <contributor> <username>internetarchivebot</username> </contributor> <comment>rescuing 1 sources and tagging 0 as dead #iabot v2095</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> a...
lusaka lusaka je oluilu ati ilu t'otobijulo ni orile-ede zambia
aristotulu aristotulu èdè grííkì ayéijọ́un onímoye araàyèíjòun omo ilé gréésì akékò plato àti olùko aléksanda eni ńlá
orílẹ̀ orílẹ̀ jẹ́ àkójọ àwọn orílẹ̀-èdè àti agbègbè ńlá àwọn orílẹ̀ tó wà lágbáyé ni asia africa north america south america antarctica europe àti australia agbegbe ati piposi àkójọ ilẹ̀ àwọn orílẹ̀ ni 148647000 km² tàbí 291 ilẹ̀ ayé 510065600 km2
internet íńtánẹ́ẹ̀tì jẹ́ asopọ̀ bí ìtakùn àwọn ẹ̀rọ kọ̀m̀pútà káàkiri àgbáyé fún ìpàṣípààrọ̀ ìpolongo àti ìmọ̀ ní èdè gẹ̀ẹ́sì ó wá láti orúkọ inter - network nítorí náà ní èdè yorùbá à ń pè ní íńtánẹ́ẹ̀tì
tessalonika thessaloniki tabi salonika je ilu ni orile-ede griisi
yúróòpù
raila odinga raila amollo odinga born january 7 1945 je oloselu omo ile kenya lowolowo o je alakoso agba ile kenya ninu ijoba idarapo a bí i ní maseno kizumu district nyanza prorince ní january 1945 ó rí ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ ní 1965 èyí tí ó fi lọ kàwé ní technical university of magdeburg tí ó jẹ́ ara otto von gueriche universi...
mwai kibaki a bí kìbákì ní ọjọ́kẹ̀ẹ̀ẹ́dógún oṣù kọ́kànlá ọdún 1931-2022 orúkọ ìbatisi rẹ̀ ni emilio stanley ṣùgbọ́n kò pé tí ó fi orúkọ yìí sílẹ̀ tí ó ń jẹ́ orúko kìkúyí òjíṣẹ́ ọlọ́run kan ara ítálì ni ó sà á lámì ọmọ ìjọ àgùdà catholic ni kìbákì history àti political science ni ó kà ní màkéréré university ní kampala u...
emeka anyaoku eleaza chukwemeka anyaoku a bí i ní 18th january 1932 ní ìpínlẹ̀ anambra ní ilẹ̀ nàìjíríà ó lọ sí ile-ẹ̀kọ́ ní merchant of light school oba university of ibadan institute of public administration london cavillam institute france ó ti ṣe minister of foreign affairs rí ó ṣiṣẹ́ ní foreign service ó jẹ secret...
felix ohiwerei felix omoikhoje aizobeoje ohiwerei je onisowo omo ile naijiria a bí i ní 18th january 1937 ní owan ní ipinle edo ní ilẹ̀ nààjíríà ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ní st david’s school arbiosi ni 1944-1946 government school owerri 1947-1950 government secondary school owerri 1951-1955 nigerian college of arts science an...
herbert macaulay herbert samuel heelas macaulay november 14 1864—may 7 1946 jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ọmọ-ọmọ bíṣọọ́ọ̀bù samuel ajayi crowther ní herbert macaulay jẹ́ a bí i ní ọdún 1864 ó gboyè ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ẹ̀rọ lórílẹ̀-èdè gẹ̀ẹ́sì ó dá ẹgbẹ́-òṣèlú sílẹ̀ lọ́dún 1923 ó kú ní ọdún 1946 níbi ti ó ti n ṣe ìpolon...
nnamdi azikiwe benjamin nnamdi azikiwe november 16 1904 may 11 1996 tabi zik jẹ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà láti ẹ̀yà igbo ọkan ninu awon ólósèlú pàtàkì ni azikiwe jẹ ni nàìjíríà o si jẹ asíwájú fun ifegbega orile-ede ara ẹni ni nàìjíríà lodeoni bẹ sini o tun jẹ aare ile naijiria akọkọ ni ìgbà òṣèlú àkọ́kọ́ ilẹ̀ nàìjíríà l...