raw_text
stringlengths
2
128k
ahmadu bello al-hajji sir ahmadu ibrahim bello june 12 1910 january 15 1966 ti òpòlopò mo sí sir ahmadu bello jé eni ti o wa nidi dida ariwa nigeria kalè nipase ominira nàìjíríà ni odun 1960 oun si ni adaripremier àkókó ati enikan soso ti o di premier ariwa nàìjirià ipò tí o di ipò náà mú títí ti won fi sékúpa ni odun ...
sir abubakar tafawa balewa
bola ige
yunifásítì yunifasiti je ile-eko giga ati isewadi ti o fun ni ni iwe-eri fun imo ijinle ni bi eyi-keyi eko to ba wuwa lati ni imo aridaju nipare
ìkàrẹ́-akóko ìkàrẹ́-akóko tabi ìkàrẹ́ ni soki je olú ìlú agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá-ìlà òrùn àkókó ní ̀ipínlẹ̀ òndó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó tún jé olú-ìlú tẹ́lẹ̀-tẹ́lẹ̀ fún gbogbo agbègbè àkókó lápapò ní ìpínlè ondó àwọn ìlú tí ó wà ní agbègbè ìkàrẹ́ tẹ́lẹ̀ ni ọ̀kà-àkókó ìṣùà àkókó ọ̀gbàgì-àkókó òkèàgbè-àkókó ìrùn-àkó...
umaru musa yar'adua umaru musa yar'adua 16 august 1951 - 5 may 2010 je aare naijiria keji ni igba oselu ekerin ni orile-ede naijiria o je gomina ipinle katsina lati 29 may 1999 titi di 28 may 2007 a kede rẹ ni olubori ninu idibo aarẹ orilẹ -ede naijiria ti o waye ni ọjọ 21 oṣu kẹrin ọdun 2007 ati pe o bura ni ọjọ 29 oṣ...
àwọn olórí ilẹ̀ nàìjíríà ṣáájú òmìnira àwon olórí ilè nàìjíríà sáájú òmìnira ni
tunde idiagbon babatunde baku abdul idiagbon 14 september 1942 - 24 march 1999 jẹ́ ọmọ ológun ará ilẹ̀ naijiria ní ọdún 1983 ó kópa nínú ifipágbàjoba lọ́wọ́ ààrẹ shehu shagari lẹ́yìn èyí ó di ọ̀gá gbogbo ọmọọṣẹ́ ológun ní ibùjókó tó ga jù lọ ní ẹgbẹ́ àwọn ológun ilẹ̀ nàìjíríà ipò yìí dúró gẹ́gẹ́ bí igbákejì ààrẹ sí muh...
alhaji sheu shagari
jacob zuma jacob zuma jẹ́ ààrẹ orílẹ̀ èdè gúúsù áfíríkà tẹ́lẹ́ ó wolé ní osù kejìlá odún 2006 gégé bí alága fún egbé african national congress anc ní guusu afrika olóyè ni ó jé ní àárín àwọn zulu ní ọjọ́ karùn-ún osù kìíní odún 2007 ó fé nompumeledo ntuli ọmọ ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n gẹ́gẹ́ bí ìyàwó rẹ̀ karin lẹ́yìn ìgbà t...
joseph h greenberg ohun tí òǹkọ̀wé ṣiṣẹ́ lé lórí nínú ìwé yìí ìpín èdè aáfíríkà sí ẹbí orí méje ni ìwé náà ní orí kìíní ni ó sọ̀rọ̀ nípa ìlàlà tí a lè tẹ̀lé láti pín èdè kan sí ẹbí lẹ́yìn èyí ni òǹkọ̀wé wá bẹ̀rẹ̀ sí ní í ṣe àlàyé àwọn ẹbí tí ó pín èdè aáfíríkà sí orí keyì sọ̀rọ̀ nípa niger-cong ẹ̀kẹ́ta afrocasiatic ẹ̀k...
àwọn ọba ilẹ̀ nàìjíríà ìlú àti orúkọ oyè wọn abẹ́òkúta - aláké adó-èkìtì - èwí àkúrẹ́ - déjì arámọkọ - alárá ẹdẹ - tìmì ìlokò - aloko ìkọ̀lé - ẹlẹ́kọ̀lé ìjerò - ajerò ilẹ̀-olújìí - jegun ìdànrè - ọwá ìkàrẹ́ - olúkàrẹ́ ifọ́n - olúfọ́n ifẹ̀ - ọọ̀ni ìbàdàn - olúbàdàn calabar - obong onitsha - obi ilẹ́sà - ọwá obòkun ìlá -...
àwòrán ará òwò nàìjíríà àwọn owó nàìjíríà àti àwòrán tí ó wà lára wọn n1 - náírà kan herbert macaulay n5 - náírà márùn-ún alhaji tawafa balewa 1912-1966 n10 - náírà mẹ́wàá alvan ikoku 1900-1971 n20 - ogún náírà murtala mohammed 1938-1978 n100 - ogọ́rùn-ún naira chief ọbáfẹ́mi awólọ́wọ̀ 1909-1987 n200 - igba naira alhaj...
àwọn olórí ìjọba ilẹ̀ nàìjíríà ààrẹ ilẹ̀ nàìjíríà 1st october 1979 ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá 1979 general olúṣégun ọbásunjọ́ fi ọ̀pá àṣẹ lé alhaji shehu shagari lọ́wọ́ 26th august 1993 ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹ́jọ 1993 general ib babangida yẹ̀bá fún chief earnest shónẹ́kan olórí ogun tí ó jẹ́ àrẹ ni bàbángida náà pe ara rẹ ...
ìjọba ìbílẹ̀ adámáwá adamawa idemsa fufore girei gombi guyuk hhong jada yola north lamurde madagali maiha mayo-bel michika-micloka mubi north-uba mubi south numan shelle song goila toungo yola south
àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìpínlẹ̀ akwa-íbọm abak abak eastern obodo eket eket atai essien udim afa he ikot etim ekpo etinan etinan ibesikpo asutan ibiono ibom ibiono ika ikono ibiaku ntokoko ikot abasi ikot abasi ikot ekpene ini odoro ikpe itu itu enwang mkpat enin mpat enin nsit ibom msit ubium akara okobo onna abat o...
àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìpìnlẹ̀ anámbra aguata aguata anambra east otuocha ananmbra west nzam aniocha neni awka north achalla awka south akwa ayamelum anaku dunukofia ekwusiewo ozubu idemili north ogidi idemili south idemoli ihiala ihia njikoka nnewi norh nnewi nnewi south ukp ogbaru onitsha north onitsha orumiba nor...
ojúewé àkọ́kọ́ <templatestyles src=main page/minervacss /> wikipedia ní àwọn èdè míràn àwọn wikipedia tí wọ́n ní ju àyọkà 1 000 000 lọ · àwọn wikipedia tí wọ́n ní ju àyọkà 500 000 lọ · · · àwọn wikipedia tí wọ́n ní ju àyọkà 100 000 lọ · · · · · · · · · · · ·
ìjọba ìbílẹ̀ nàìjíríà naijiria ní ìjọba ìbílèlgas 774 ikokan àwọn ìjọba ìbílè yìí sì ni ó wà lábé ìdarí alága àti àwọn ìgbìmò tí à ún pè ní councilors ikokan àwọn ìjọba ìbílè ní wón pín sí ó kéré jù èka mẹwa sí ogún àwọn councilors ló ún ṣe àkóso àwọn ẹ̀ka kokan wón sì ún fi àbọ̀ já alága èyí ni àtòjọ àwọn ìjọba ìbílè ...
kudirat abiola kúdíràtù abíọ̀lá tí a bí ni ọdún 1951 dágbére fáyé ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹfà ọdún 19961951 - 4 june 1996 jẹ́ òṣèlú àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọ ènìyàn ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó tún jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìyàwó m k o abíọ́lá ayé rẹ̀ wọ́n bí i ní ọdún 1951 ní zaria ní ilẹ̀ nàìjíríà alhaja kudirat abiola ni obìnrin kejì t...
ariwa afrika
alex ibru alexander uruemu ibru march 1 1945 - 20 november 2011 je onisowo omo ile naijiria ohun tun ni oludasile iweroyin ojojumo the guardian newspapers ti o dasile ni 1983
hogan bassey hogan kid bassey 1932-06-03 - 1998-01-26 je omo ile naijiria oruko ti a so ni okun asuguo bassey ní ọdún 1952 ọwọ́ nàìjíríà kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ hogan bassey di world featherweight champion ní ìlú òyìnbó
táyọ̀ awótúsìn tayo awotusin táyọ̀ awótúsìn àti chris odiiibe níbi ogun tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní leberia wọ́n pa táyọ̀ awótúsìn ti ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn champion àti chris odiiibe ti ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn guardian ní ọdún 1991 níbi tí wọ́n ti ń ṣe iṣẹ́ òòjọ́ wọn gbigbesele iwe iroyin ní oṣù kéje ọdún 1993 ìjọba àpapọ̀ gbẹ́sẹ̀ lé tí...
délé giwa nigerian journalist and newspaper founder dele giwa tí abísọ rẹ̀ ń jẹ́ sùmọ́nù ọládélé baines giwa jẹ́ ọmọ prílẹ̀-èdè nàìjíríà tí won bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹta ọdún 1947 tí ó sì papò dà ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹwá ọdún 1986 16 march 1947 19 october 1986 jẹ́ oníṣẹ́ ìwé ìròyìn àti olóòtú ìwé ìròyìn ọ...
fifa egbe ipapo kariaye ajose boolu-elese geesiinternational federation of association football faranse fédération internationale de football association to gbajumo gege bi fifa ni is the international agbarajo asejoba kariaye fun boolu-elese ibujoko re wa ni zürich switzerland be sini aare re lowolowo bayi ni sepp bla...
jàjá ìlú òpobò jaja ilu opobo ọba jaja tí ìlú opobo orúkọ jubo jubogha 1821 - 1891 jẹ́ ọmọba oníṣòwò òun sì ní olùdásílẹ̀ ìlú opobo tí ó wà ní ìlú ìpínlẹ̀ rivers tí ìlú nàìjíríà wọ́n bí ni umuduruoha amaigbo ní ìpínlẹ̀ imo ọ̀dọ̀ ló wà nígbà tí àwọn afẹ́rú-ṣòwò mú lẹ́rú ní bonny orúkọ tó padà jẹ́ ni jájá jaja of opobo n...
irinkerindo ninu igbo elegbeje ti do fagunwa ko
kenya kẹ́nyà tàbí orile-ede olominira ile kẹ́nyà je orile-ede ni ìlaòrùn áfríkà o dubule si eba okun india ni agedemeji aye kẹ́nyà ni bode mo ethiópíà ariwa sòmálíà ariwailaorun tànsáníà guusu ùgándà ati lake victoria iwoorun ati orile ede gúúsù sudan ariwaiwoorun oluilu re ni nairobi awon onibugbe ibe ti po to 38 legb...
john harrison burnett john burnett tí ó jẹ́ principal àti vice-chancellor university of edinburgh láàrin 1978 sí 1987 kú ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kéje ọdún 2007
mọfọ́lọ́jì èdè yorùbá mọfọ́lọ́jì ìfáárà ìpele tàbí ìsọ̀rí márùn-ún ni a lè pín gírámà èdè sí àwọn ìpèle yìí náà ni fònẹ́tíìkì tàbí ètò ṣíṣàpèjúwe ìró fonọ́lọ́jì tàbí ìbáṣepọ̀ ìró sẹ̀méńtíìkì tabí èt`o ìtumọ̀ síntáàsì tàbí ètò tí ó dale gbólóhùn àti mọfọ́lọ́jì tabí ètò nípa ṣíṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ gbogbo àwọn ìpele wọ̀nyí ni ó ní...
ng ng je amioro orile-ede fun top-level domain ti internet cctld fun naijiria
ṣáínà
kúbà kúbà tabi orile-ede olominira ile kuba pípè /ˈkjuːbə/ spánì je orile-ede erekusu ni karibeani orile-ede kuba ni erekusu kuba gbangba isla de la juventud ati awon sisupapo-erekusu havana ni ilu titobijulo nibe ati oluilu re santiago de cuba ni ilu keji totobijulo
cuba
benin benin pípè /bɨˈnɪn/ tàbí orílẹ̀-èdè olómìnira ilẹ̀ benin jẹ́ orílẹ̀-èdè ní ìwọ̀orùn áfríkà ó ní bodè pẹ̀lú togo ní apá ìwọòrùn nàìjíríà ní apá ìlaòrùn àti burkina faso àti nijẹr ní àríwá ní gúúsù ó jásí etíòkun benin bight of benin itobi re ko fi be ju lo pelu arabudo to fe e to 8500000 botileje pe oluilu re je p...
ilẹ̀ ọba benin ilẹ̀ ọba benin tabi ile oba edo 1440-1897 je ilu oba ayeijoun ni apa arin iwoorun ibi ti a mo si naijiria loni
ilú-ọba ọ̀yọ́ former empire in present-day benin and nigeria ilẹ̀ ọba ọ̀yọ́ jẹ́ ikan pataki lara ilẹ̀ yorùbá ni apá iwọ̀ oorùn ilẹ̀ adúláwọ̀ idagbasoke ilẹ ọba ọyọ ko sé lẹyin bi wọn ṣe ni agekale oun itọsẹ iṣejọba to lọọrin ti wọn fi n tolu ati awọn ilu amọna ti wọn wa labẹ iṣakoso wọn laye atijọ bakan naa ni wọn n ṣe...
gr gr jẹ́ àmì ọ̀rọ̀ orílẹ̀-èdè fún ìpele tí ó ga jùlọ tí ẹ̀rọ ayélujárá cctld fún orílẹ̀-èdè gèésì
gíríìsì gíríìsì gíríkì elláda èdè grííkì ayéijọ́un hellás bakanna gege bi hellas ati fun ibise bi helleniki olominira ελληνική δημοκρατία ellīnikī́ dīmokratía je orile-ede kan ni guusuapailaorun europe o budo si apaguusu opin balkan peninsula griisi ni ile bode mo albania olominira ile makedonia ati bulgaria si ariwa a...
ac ac
ad ad je ti ile andorra
ae ae
af af je ti orile-ede afghanistan
ag <id>10425</id> <revision> <id>20532</id> <timestamp>2008-02-26t175735z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <comment>new page {{ flag/core | alias = antigua and barbuda | flag alias = flag of antigua and barbudasvg | flag alias-colonial = antiguaflaggif | flag alias-naval ...
ai ai je ti ile anguilla
al al je ti ile albania
zm zm je ti orile-ede zambia
zw zw
am am je ti ile armenia
an an je ti ile netherlands antilles
ao ao
aq aq
ar ar
as as
at at je ti ile austria
au au je ti orile-ede australia
aw aw
ax ax
az az
ba ba
bb bb
bd bd je ti orile-ede bangladesh
be be je amioro lori internet fun belgium
bf bf
bg bg
bh bh je ti ile bàhàréínì
bi bi
bj bj je ti ile benin
bm bm je ti ile bermuda
bn bn
bo bo je ti ile bòlífíà
br br je ti ile brasil
bs bs je ti ile bahamas
bt bt ni amioro orile-ede ti internet fun top-level domain cctld fun orile-ede bhutan
bv bv
bw bw je ti orile-ede botswana
by by je ti orile-ede belarus
bz bz je ti ile bẹ̀lísè belize
ca ca
àkójọ àwọn orílẹ̀-èdè bi iye mọ̀ọ́kọmọ̀ọ́kà
estóníà estonia tabi orile-ede olominira ile estonia je orile-ede ni apaariwa europe
ede geesi
ede geesi
ìgbìmọ̀ òlímpíkì akáríayé ìgbìmọ̀ òlímpíkì oníkíkáríayé ioc ni ede geesi duro fun international olympic committee je egbe ikojo to budo si lausanne ni orile-ede switzerland ti pierre de coubertin ati demetrios vikelas dasile ni 23 june odun 1894 awon omo egbe je awon 205 igbimo olympiki ti awon orile-ede
àwọn ìdíje òlímpíkì idije olympiki {tabi olympiki} je opolopo ere idaraya ti won sele ni igba ooru ati igba otutu won n sele lekan larin odun merin titi di 1992 ninu odun kanna ni won n sele lat'igbana won ti ya won soto pelu odun meji awon idije olympiki ede greeki ολυμπιακοί αγώνες olympiakoi agones akoko waye ni odu...
tógò togo tabi orile-ede togo olominira je orile-ede ni iwoorun afrika o ni bode mo ghana ni apa iwoorun benin ni apa ilaoorun ati burkina faso ni ariwa
global positioning system global positioning system gps sistemu siseipo laye je onailana itoka ipo ohunkohun l'ori ile-aye pelu satellite
gps
ronald reagan ronald wilson reagan february 6 1911 june 5 2004 je aare ogoji orile-ede ìsọ̀kan àwọn ìpínlẹ̀ ilẹ̀ amẹ́ríkà 19811989 ati gomina eketalelogbon ipinle kalifonia 19671975
àwọn ìpínlẹ̀ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà àwọn ìpínlẹ̀ amẹ́ríkà jẹ́ àwọn ìpínlẹ̀ àádọ́ta tó para pọ̀ di orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà
ìwé-òfin ìbágbépọ̀ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà iwe-ofin ibagbepo orile-ede amerika je ofin to gajulo ni orile-ede ipinle isokan ile amerika
usa
alábùgbé alábùgbé tabi olùgbé tabi iye olùgbé ninu imo awujo ati imo biology je akojopo awon eniyan tabi awon irú ohun kan pato iye aráàlú
ìjọ kátólìkì ìjọ kátólìkì tí a tún ń pè ní ìjọ àgùdà tàbí ìjọ kátólìkì róòmù
plato plato greek plátōn broad 428/427 bca 348/347 bc was a classical greek philosopher mathematician student of socrates writer of philosophical dialogues and founder of the academy in athens the first institution of higher learning in the western world along with his mentor socrates and his student aristotle plato he...
olúìlú oluilu je ilu ti ijoba orile-ede kan fi se ibujoko o tun le tumo si ilu ti o ba tobi ju lo tabi ti o se pataki ju lo ni agbegbe orile-ede tabi ipinle kankan fun apere awon olu ile ti o se pataki julo ni aiye je new york ni orile ede amerika ati london ni orile ede awon geesi ni ile erekusu{continent} africa ilu ...
ìlú òbè-nlá ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ìlú òbè-ńlá olúbákin ni orúkọ ẹni àkọ́kọ́ tí ó jẹ olúbo ní òde ugbo ìtàn sọ pé àtọmọdọ́mo sẹ̀pẹ̀lúwà tí ó jẹ́ awùjalẹ̀ ìkejìdínlógún ti ilẹ̀ ìjẹ̀bú ni olúbákin jẹ́ olúbákin àti àbúrò rẹ̀ tí wọ́n jọ jẹ́ ọmọ bàbá ni wọ́n jọ dunpò awùjalẹ̀ ìkẹtàdínlógójì ti ilẹ̀ ìjẹ̀bú lẹ́yìn tí ọba morógbèsọ̀ a...
abrahamu abrahamu hébérù אַבְרָהָם avraham ʾaḇrāhām lárúbáwá ‎ ibrāhīm ʾabrəham ni eni tí ó dá ilẹ̀ àwon júù sílè wọ́n bí i ní ur ọmọ terah ni abram ó sí ló sí haran ní gusu mesopotama pẹ̀lú bàbá rẹ̀ ìyàwó rẹ̀ sarah àti lot tó jẹ́ ‘nephew’ rẹ̀ nígbà tí ó lọ sí kénáànì ó gbọ́ ìpè jehovah pé ibẹ̀ ni ilẹ̀ ìlérí fún àwọn è...
òkè abu oke abu je ibi togajulo ni ori aravalli to wa ni ipinle rajasthan ni apaiwoorun india