raw_text
stringlengths
2
128k
argẹntínà argẹntínà nínú ètò ìkànìyàn 1995 iye àwọn ènìyàn tí ó wà ní orílẹ̀-èdè ajẹntínà argentiana lé díẹ̀ ní mílíọ̀nù mẹ́rìnlélógójì àti àti ààbọ̀ 46 245 668 èdè pànyán-àn ni èdè tí wọ́n fi ń ṣe ìjọba ní ibẹ̀ àwọn èdè mìíràn tí wọ́n tún ń sọ ní orílè-èdè yìí lé ní ogún lára àwọn ogún èdè yìí ni àwọn èdẹ̀ tí wọ́n ń p...
èdè árámáìkì èdè árámáìkì je ara èdè sèmítíìkì semitic àwon tí ó ń so èdè yìí tó egbèrún lónà igba ní ìráànù iran àti ìráàkì iraq pèlú òpòlopò àwon mìíràn tí wón tún ń so ó ní ààrin gbùngbùn ìlà-òòrùn àgbáyé middle tast láti séńtúrì kefà ni wón ti ń fi árámáìkì àtijó classical aramaic ko nnkan sílè ní ààrin gbingbein ì...
arabic
èdè lárúbáwá èdè lárúbáwá tabi ede araabu ara èdè sẹ̀mítíìkì ni èdè àrábíìkì arabic èdè lárúbááwá àwọn tí ó ń sọ ọ́ tó mílíọ̀nù lọ́nà igba gẹ́gẹ́ bí èdè abíníbí ní àríwá aáfíríkà àti ìlà-oòrùn-gúsù eésíà asia àìmoye ènìyàn tí a kò lè fi ojú da iye wọn ni ó ń sọ èdè yìí gẹ́gẹ́ bí èdè kejì ìyẹn èdè àkọ́kún-tẹni ní pàtàkì...
ántígúà àti bàrbúdà ántígúà àti bàrbúdà pípè /ænˌtiːgwə æti bɑːɹˈbjuːdə/ spani fun atijo ati onirungbon je is a twin-orile-ede erekusu-meji larin omi-okun karibeani ati okun atlantiki o ni erekusu meji ninla ti awon eniyan ungbe be ántígúà ati bàrbúdà pelu awon erekusu kekeke melo kan bi awon erekusu great bird green g...
angola àngólà lóníbiṣẹ́ bíi orílẹ̀-èdè olómìnira ilẹ̀ àngólà kikongo kimbundu umbundu repubilika ya ngola jẹ́ orílẹ̀-èdè kan ní apágúsù áfríkà tó ní bodè mọ́ namibia ní gúsù orílẹ̀-èdè olómìnira olóṣèlú ilẹ̀ kóngò ní àríwá àti zambia ní ilàòrùn ìwọ̀òrùn rẹ̀ bọ́ sí etí òkun atlántíkì luanda ni olúìlú rẹ̀ ìgbèríko òde kà...
àndórà àndórà tabi fun iseoba o je ilẹ̀-ọmọba andorra bakanna won tun mo si ilẹ̀-ọmọba àwọn àfonífojì ilẹ̀ àndórà principality of the valleys of andorra je orílẹ̀-èdè aláfilẹ̀yíká ni apa guusuiwoorun europe nínú ètò ìkànìyàn 1995 àwọn tí ó ń gbé àndórà jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjì-dún-láàádọrin 68000 àwọn èdè tí ó jẹ́ ti ìjọba ní...
amóráìtì amorite je èdè sẹ̀mítíìkì semitic kan ni amóráìtì amorite tí wọ́n ń sọ ní agbègbè àríwá síríà syria òde òní ní nǹkan bí ẹgbẹ̀rún méjì ọdún sí ẹgbẹ̀rún kan àbọ̀ ṣáájú ìbí kírísítì díẹ̀ ni a mọ̀ nípa èdè yìí nítorí pé láti inú orúkọ ènìyàn àti àwọn àkọ́sílẹ̀ díẹ̀ tí a rí tí wọ́n opẹ́ sí ara òkúta nìkan ni a mọ̀ ...
èdè àmháríkì amhariki èdè sẹ̀mítíìkì semitic kan ni eléyìí tí nǹkan bú mílíọ̀nu márùndínlógún ń sọ gẹ́gẹ́ bí èdè àkọ́kọ́ ní ethopia ìtópíà níbẹ̀ wọ́n ń lò ó gẹ́gẹ́ bí tí ìjọba ń mú lò àwọn bú mílíọ̀nù márùn-ún ni ó ń sọ èdè yìí ní agbègbè ethiopia nígbà tí ̣ àwọn ọ̀pọ̀lọpò mílíọ̀nù mìíràn ń sọ èdè yìí gẹ́gẹ́ bí èdè kej...
àngúíllà anguilla nínú ètò ìkànìyàn 1995 àwọn ènìyàn tó wa ní anguilla jẹ́ ẹgbẹ̀rún méje àti ọgọ́rùn-ún 7100 èdè gẹ̀ẹ́sì ni wọ́n ń sọ níbẹ̀ púpọ̀ nínú àwọn ènìyàn ibẹ̀ ni wọ́n ń sọ èdè kirió tí wọ́n gbé ka èdè gẹ̀ẹ́sì english based creole kirió yìí ni ó wọ́pọ̀ jù ní áńtílẹ́ẹ̀sì lesser antilles
olódùmarè olódùmarè káàkìri àgbáyé ni a ti mò pé olódùmarè wà eni tí ó dá ayé àti òrùn àti ohun gbogbo ti ń be nínú won òyígíyigí oba àìrí arínú-róde olùmòràn òkàn alèwílèse alèselèwí oba atélè bí eni téní oba atésánmo bí eni téso oba lónìí oba lóla oba títí ayé àìnípèkun olówó gbogbogbo tí ń yomo rè nínú òfin oba olój...
koisaanu oju=iwe kiini ọlọfnsao olukemi m àwọn ẹbí èdè khoisan ìfáàrà ẹbí èdè khoisan yìí ni ó kéré jù lọ nínú àwọn ẹbí èdè gbogbo tí ó wà ní áfíríkà gẹ́gẹ́ bí greenberg 1963a ti sọ ó ní àwọn ni wọ́n dúró fún èyí tí ó kéré jù lọ nínú èdè áfíríkà ìpìlẹ̀ orúkọ èdè yìí a mu orúkọ yìí jáde láti ara orúkọ ẹgbẹ́ khoi-khoi ti...
nigeria
ilorin ilorin ni olu-ilu ìpínlẹ̀ kwara ní ìwọ̀ oòrùn nàìjíríà gégé bi abayori ìkà ènìyàn odun 2006 ní nàìjíríà ìlú ilorin ní olùgbé 777667 èyí mú kí ó jẹ́ ìlú keje tí ó ní olùgbé jùlo ní nàìjíríà
kazimierz nowak kazimierzu nowaki lati ọdún 1897 títí di osu òwàrà ọjọ kétàlá ọdún 1937 je ọmọ ìuí polandi ti ọjẹ arińninajo oníweroým ati aya woran ti a bi ni ilu stiryi lehin ogun àgbáyé alakọkọ ogbe ni ilu poznani lati ọdún 1931 títí di ọdún 1936 orin ogun kẹkẹ jake jado ilu aláẁọ dúdú orin irinajo ti oto egberun lọ...
lítíréṣọ̀ litireso tabi iṣẹ́ọnàmọ̀ọ́kọmọ̀ọ́kà ohun tí lítíréṣọ̀ jẹ́ eléyìí náà kò ṣàì ní orírun tirẹ̀ láti inú èdè látìn “litere” èyí ni àwọn gẹ́ẹ́sì yá wọ inú èdè wọn tí wọ́n ń pè ni lete rature” ìtumọ̀ tí a fún lítíréṣọ̀ máa ń yípadà láti ọ̀dọ̀ ẹ̀yà ènìyàn kan sí èkejì láti ìgbà dé ìgbà lítíréṣọ̀ kò dúró sójú kan bab...
ìjẹ̀ṣà àwọn ìjẹ̀ṣà je iran kan nínú àwọn ọmọ yorùbá ipinle osun ni nigeria ni won budo si julo ìtàn tí a bá ń sọ̀rọ̀ nípa ojúlówó àwọn ọmọ yorùbá ni ilẹ̀ yorùbá òde-òní ìjẹ̀sa jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára ojúlówó ọmọ yorùbá tí kò se fí ọwọ́ rọ́ sẹ́yìn nínú ìtàn àwọn yorùbá oríìsíìsí ìtàn ni a sì gbọ́ nípa orírun ìjẹ̀sà gẹ́gẹ́...
iléṣà iléṣà jẹ́ ìlú ní ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ tí a bá ń sọ̀rọ̀ nípa ojúlówó àwọn ọmọ yorùbá ni ilẹ̀ yorùbá òde-òní ìjẹ̀sa jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára ojúlówó ọmọ yorùbá tí kò se fí ọwọ́ rọ́ sẹ́yìn nínú ìtàn àwọn yorùbá oríìsíìsí ìtàn ni a sì gbọ́ nípa orírun ìjẹ̀sà gẹ́gẹ́ bí ojúlówó yorùbá kó dà ...
ẹ̀gbá ẹ̀gbá je eya yoruba ni naijiria ilẹ̀ ẹ̀gbá ó se pàtàkì láti mọ díẹ̀ nípa ìtàn ilẹ̀ ẹ̀gbá àti irú ènìyàn tí ń gbé ìlú ẹ̀gbá ìdí èyí ni pé yóò jẹ́ ohun ìrànlọ́wọ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan tó yẹ ní mímọ̀ nínú orin ògódò fún ìdí pàtàkì yìí n ó ò pín àkòrí yìí si ọ̀nà mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ìtàn ẹ̀gbá ọ̀pọ̀lọpọ̀ onímọ̀ ló ti s...
ilẹ̀ ọba bakuba ilẹ̀ọba bakuba o tun nje kuba tabi bushongo ifáárà àwọn kúbà náà ló ń jẹ bushoong ààyè wọn ààrin gbungban gusu congo zaire ni wọ́n wà iye wọn ẹgbẹ̀riún mẹ́tà-dún-lóguń ni wọn èdè wọn ede bushhoog ló jẹ́ ẹ̀yà bàǹtú ni wọn ń sọ alágàágbe wọn biombo lùbà kasai lenda pyaang àti ngongo ìtàn wọn awọn bushoog ...
kuwere kwere kuwere ààyè wọn wọ́n wà ní apa ìwọ-oòrun ààrin gbuǹgbùn tanzania iye wọn wọn lè ní ẹgbẹ̀rún lọ́nà ààdọ́ta eǹìyàn èdè wọn èdè kikwer ti bàǹtú ni wọ́n ń sọ alábàágbé zaramọ doe zingna luguru àti swahili ìtaǹ wọn ní nǹkan bí ẹgbẹ̀rún ọdún ṣẹ́yìn ni baba ńlá kwere de láti mozanbiquenínú ìrìn-àjò wọn ni wọ́n ti...
kiwahu kwahu kiwahu àáyè wọn wọ́n wà ní apá àríwá ghana iye wọn wọ́n lé ní ẹgbẹ̀rún márún lé lọ́gọ́ta èdè wọn ède akàn ti ẹ̀yà twini wọn ń fọ̀ alábàágbé wọn anyi asante àti fante ítàn wọn ẹ̀yà akan tó ń gbé àríwá ghana ni kwahu ìjọba ńlá akàn bẹ̀rẹ̀ ní nǹkan bí sẹ́ńtúrì mẹ́tàla sẹ́yìn àsìkò yìí ni ìjọba ńlá asanti bẹ̀r...
laka laka laka ààyè wọn grúsù ìls̀ oòrùn chad ni wọ́n wà iyè wọn ẹgbèrún lọ́nà ọgóruǹún èdè wọn lake àti mbonu niger-congo ni wọ́n ń ṣo alábàágbé wọn sára èèyan cameroon àti fúlaní ni múlé tí wọ́n itan wọn àríwá ìlà oòruń oko chad ni wọ́n ti ṣẹ ijọba ńlá tí fúlàní ló wọn dèbi wọ́n wà yìí èdè àti aṣa wọn àti ti cameroon...
luba luba ààyè won àríwa iwọ oòrùn congo zaire iye wọṅ mìlíonù kan èdè wọṅ cilube ààrin gbùngbùn bantu alábàágbé wọn chowe ndembu kaonde benba tabwa songye lunda itan wọṅ ijọba ńlá luba ti bẹ̀rẹ̀ ní nǹkan bí ẹgbẹ̀rún kan ààbọ̀ ọdún sẹ́yin 1500 ìjọba yìí ń gbòòrò láti upemba tí í ṣe ààrin gbuńgbún lube wọn fẹ̀ dé iòkè t...
bangubangu bangubangu je eya kan ni afrika èdè wọn ni wọn ń pè ni bantu wọ́n tún lè pè é ni kiban gubangu èdè yìí pin si ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta 500 ede méjìlá nínú èdè bantu ni ògọ̀ọ̀rọ̀ àwọn ènìyàn tó lè ni mílíọ́ọ́nù márùn-ún ń sọ lára àwọn tí ó ń sọ èdè bantu ni rundi rwanda shona xhosa àti zulu swalili èdè olóhùn ni èdè yìí...
baule baule tabi baoule je eya eniyan ni afrika baule jẹ́ àwọn ènìyàn akan tí a lè rí ní ghana àti cote d'ivoire èdè wọn ni kwa tí ó jẹ́ ọ̀kan nínú èdè tí ó wà ẹ̀yà niger congo èdè kwa jẹ́ èdè àdúgbò àwọn akan àwọn baule náà máa ń sin àwọn òrìṣà iṣẹ́ àgbẹ̀ ni iṣẹ́ wọn
beembe beembe àwọn beembe ń gbé ni àríwá zaire ni congo brazzaville ọ̀nà méjì ni wọ́n ti wá sí beembe àwọn kan ti ń gbe ibẹ̀ láti ọdún 1485 nígbà tí àwọn yapa láti congo nígbà ogun portuguese ni ọdun 1665
betsileo àwọn betsileo jẹ ẹ̀yà ará àwon àfíríkà tí wọ́n ń gbe ní madagascar àgbẹ̀ ni wọn wọ́n máa ń gbé nínú ahéré ti wọ́n fi ewé ṣe wọ́n ń ṣe iṣẹ́ gbẹ́nàgbẹ́nà ó jẹ́ ìkan nínú àwọn èdè malagasy
betsimisaraka betisimisaraka je eya malagasy ó jẹ́ èdè kan lára èdè malagasy iṣẹ àgbẹ̀ ni àti iṣẹ́ ọkọ̀ ojú omi wiwa sailor àti olè ojú omi pirate láàrin ẹ̀yà madagascar àwọn ẹ̀yà betsimisaraka jẹ́ ẹ̀yà kejì tí ó tóbi jù
sadiiki chadic gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ new man 1992253 ó ṣọ́ pe o to nǹkan bi ogóje èdè chadic gẹ́gẹ́ bí maapu ṣeṣe àfihàn ó tanka èka mẹ́fa nínú ajúwe lati adagun odo chad nibi tí orúkọ ìdílé ti sẹ̀ wa ti a ṣi ń sọ ni apá kan nìjìríà chad cameroon orílẹ̀ èdè arìngbùngbùn ilẹ́ áfíríkà olómìnira àti niger èyí tí ó dára ju tí ó ...
sẹ̀mítíìkì semitic semitiiki semitic ni àwọn ènìyàn ka ju ti o ṣi ye wọn jù síbẹ̀ àwọn èdè kan wa ti wọn kò mọ rárá nipá ṣiṣe arópò extant ati extinet kan semitic ṣe ipatẹ adọọfa lorisiirisi nípa ìṣàkóṣo ti ìbílẹ̀ wọn ṣùgbọ́n dọsini kan àbọ̀ lo wà lábẹ́ ìṣàkóṣo àwọn arabiki ṣùgbọ́n àwọn kan rò wípé ko ba ojú mu lati ṣe...
kusitiiki cushtic kusitiiki kí á to lè ri chustic gẹ́gẹ́ bí ìdílé kan ó ní ṣe pé kí á pápọ̀ pẹ̀lú ẹgbẹ́ ìsọ̀rí èdè yòókù díẹ̀ nínú wọn dá hàn yàtọ̀ láàrín ara wọn àwọn kan ṣe àfihàn tí ó dádúró tí ó ṣi yàtò láàrín ẹ̀ka egbẹ́ ó ṣì ṣúnmọ́ atodefimọ èdè díẹ̀ laarin àwọn àgbà ẹgbẹ́ odẹ ni kenya lo ń ṣọ yaaku àwọn ẹgbẹ́ méé...
àwọn èdè niger-kóngò àkójọpọ̀ èdè tí a mọ̀ sí niger-congo dín mẹ́rin ni òjì-lé-légbéje grimes 1996 ríi gẹ́gẹ́ bíi èyí tí ó tóbi jùlọ ní àgbáyé àti wí pé àwọn èèyàn tí ó ń sọ ọ̀kan tàbí èkejì nínú àwọn èdè yìí fọ́n ká orílẹ̀ ayé ju àwọn ìyókù akẹgbẹ wọn lọ ní orílè èdè afíríkà àwọn èdè tí ó ní èèyàn tí ó pọ̀ jùlọ ni wọ́...
kodofanianu kordofanian kodofanianu ní agbègbè orí òkè nuba ní orílẹ̣̀ èdè sudan ni àwọn ènìyàn tí ó n sọ èdè yìí wọ́pọ̀ sí jùlọ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ogun àti ọ̀tẹ̀ ti fọ́n ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn yìí ká àtẹ ìṣàlẹ̀ yìí ni ó ṣe àkójọpọ̀ àwọn ìsọ̀rí èdè tí ó wà ní abẹ́ ori èdè kordofanian nínú àtẹ yìí a rí ‘proto-kordofanian...
mande ìwọ̀ oòrùn áfíríkà ni àwọn ènìyàn tí ó ń sọ èdè yìí sodo sí jùlọ àwọn ìhú tí a sì ti rí àwọn tí èdè wọn pẹ̀ka láti ara orí èdè yìí ni mali cote d’ivoire sierra leone liberia burkina faso senegal gambia guinea bissau mauritania banin ghana togo ati nigeria dwyer 1989 kastenholz 1991/2 ó tó ènìyàn bíi mílíọ̀nù mẹ́w...
àtìláńtíìkì àtìláńtíìkì atlantic gẹ́gẹ́ bí orúkọ rẹ̀ ti fi ara hàn ìwọ̀ oòrùn áfíríkà ní ẹ̀bá òkun àtìláńtíìkì ni èdè yìí sodo sí jùlo ó fọ́nká láti ẹnu odò senegal títí dé orílẹ̀ èdè liberia díẹ̀ lára àwọn èdè tí ó pẹ̀ka sí abẹ́ orí èdè yìí ni a ti rí fulfulde wolof diola serer àti remne sapir 1971 ni ó ṣe àgbékalẹ̀ à...
ijọidi apá gúúsù ilẹ̀ nigeria ni a ti rí àwọn tí wọ́n ń sọ èdè yìí èdè náà ni a mọ̀ sí defaka àti ijọ jenewari àti williamson 1989 ni wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ àtẹ isálẹ̀ yìí nínú àtẹ yìí a rí ‘proto-ijoid’ tí ó pín sí defaka ati ijọ ijọ pín ìlà-oòrùn àti ìwọ̀ oòrùn lábé ìlà-oòrùn ni a ti rí nkọrọ ibani kalabari kirike okrika ...
dogon style=background-color #b0c4de | èdè dogon languages dogon àwọn ènìyàn bíi ìdajì mílíọ̀nù tí a bá pàdé ní ilẹ̀ mali àti burkina faso ni wọ́n n sọ èdè yìí bendor-samuel àti àwọn ìyókù 1989 ni ó gbé àtẹ yìí kalẹ̀ ínú àtẹ yìí a rí ‘proto dogon’ ti o pín ṣi ìsọ̀rí mẹfa àwọn ìsọ̀rí náà nìwọ̀n yìí a plain - jamsay tegu...
krumen orílẹ̀-èdè cote d’ivoire àti liberia ni a ti lè rí àwọn ènìyàn tí wọ́n ń sọ èdè yìí ó tó ènìyàn bíi mílíọ̀nù kan sí méjì tí wọ́n ń sọ èdè yìí tí a bá wo àtẹ ìsàlẹ̀ yìí a ó ṣe alábápàdé àwọn èdè bíi kuwaa tiegba seme àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ lára orí èdè ‘kru’ nínú àtẹ yìí a rí ‘proto-kru’ tí ó pín sí ìsọ̀rí mẹ́ta àwọn...
adámáwá-ubangi i èdè tí ó gbòòrò ni èdè adamawa-ubangi ipẹ̀ka rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ láti apá gúsù-ìwọ̀ oòrùn nàìjíríà títí dé àríwá-ìwọ̀ oòrùn sudan àpapọ̀ iye àwọn tí ó ń sọ èdè adamawa tó mílíọ̀nù kan àti ààbọ̀-crozier àti blench 1992 grimes 1996 mílíọ̀nù méjì lé lẹ́gbẹ̀rún lọ́nà ọ̀ọ́dúnrún ni barreteau àti monino 1978 tọ́ka sí...
àwọn èdè bẹ́núé-kóngò ẹ̀ka méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni èdè yìí ni ìwọ̀-oòrùn àti ìlà oòrùn benue-congo àwọn orílẹ̀ èdè púpọ̀ ni ó ní àwọn èèyàn tí wọ́n ń sọ èdè yìí ó sì sodo sí apá gúúsù ilẹ̀ nigeria dáadáa bẹ́ẹ̀ náà ni ìlú bíi cameroon congo car drc tonzania uganda kenya mozambique angola rwanda burundi namibia zambia malawi ...
asa yoruba
mangbetu mangbetu àwọn ènìyàn yìí wà ní abala àríwá congo wọ́n sì tó ọ̀kẹ́ méjì ni iye èdè mangbetuti ni wọ́n ń sọ wọ́n sì múlé gbe àwọn azande mbuti àti momvu ọ́ jọ pé orílẹ̀ èdè sundan ni wọ́n ti sẹ̀ wá àgbẹ̀ ọdẹ àti apẹja sì ni wọ́n òrìṣà kilima tàbí noro ni wọ́n ń bọ gẹ́gẹ́ bí ẹlẹ́dàá wọn a sì máa bọ ara náà
lunda àwọn ẹ̀yà yìí wà ní orílẹ̀ èdè congo zambia àti angola èdè wọn sì jẹ́ ẹ̀yà ti bantu wọ́n dín díẹ̀ ní ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án wọ́n sì múlé gbe ẹ̀yà yaka suku chokwe abbl a rí àgbẹ̀ apẹja àti onísòwò tààrà ni orílẹ̀ èdè yìí mwaat yaav ni ọba wọn àwọn ìjòyè náà sì wà baálẹ̀ kọ̀ọ̀kan náà sì sà ṣùgbọ́n ìsákọ́lẹ̀ pọn dandan wọ...
luwaluwa lwalwa lwalwa luwaluwa àwọn ènìyàn yìí tó bíi ọ̀kẹ́ kan ní iye ẹ̀yà èdè bantu sì ni wọ́n ń sọ àdúgbò congo ni wọ́n wà wọ́n sì múlé gbe salampasu mbagani kete lunda luba àti chokwe wọn a máa ṣe àgbẹ̀ àti ọdẹ wọn a sì máa ṣe iṣẹ́ ọnà wọ́n ní ìgbàgbọ́n nínú olódùmarè mvidie mukulu àti ẹlẹ́dàá nzambi ṣùgbọ́n wọ́n ...
maasai style=background-color #b0c4de | èdè maa ɔl maa style=background-color #b0c4de | ẹ̀sìn monotheismincluding christianity style=background-color #b0c4de | ẹ̀yà abínibí bíbátan samburu maasai je eya awon eniyan ni apailaoorun afrika wọ́n wà ní àdúgbò orílẹ̀ èdè tanzania àti kenya wọ́n sì fẹ́ẹ̀ tó ọ̀kẹ́ mẹ́tàdínlógú...
mahafali mahafali àwọn ènìyàn yìí lé ní mílíọ̀nù kan àti ààbọ̀ wọ́n ń gbé ní apá gúúsù ìwọ̀ oòrùn madagascar àgbẹ̀ àti darandaran sì ni wọ́n wọ́n gbajú gbajà fún fínfín àti kíkun ibojì/sàréè wọ́n ní ìgbàgbọ́ nínú òrìṣà àkúnlẹ̀bọ asòdì sí ẹ̀kó kristiẹni ni ìjọba wọn tẹ́lẹ̀ wọn kò ní àǹfààní láti gbọ́ nípa orúkọ jesu nís...
makonde makonde èdè bàntú ni wón ń so wón sì wà ní tanzania àti mozambique àwon mwera makua àti mabia ni àwon alámùúlégbé won isé won sì ni àgbè ode àti igbá fínfín abúlé kòòkan ni ó sì ní baálè tirè àwon alálè ni wón sì máa ń bo bíi olórun ti won
mambila mambila àwọn ènìyàn yìí wà ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ati kamẹrúùnù wọ́n tó ẹgbẹ̀rún lọ́na mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n wọ́n sì múlé ti àwọn ènìyàn bíi kaka tikong àti bafum èdè mambila ẹ̀yà bantu ni wọ́n sì ń sọ àgbẹ ọdẹ apẹja àti ọ̀ṣìn ẹran ni ìṣe wọn ẹ̀sìn mùsùlùmí àti ti ìbílẹ̀ ni wọ́n ń ṣe papọ̀ àwọn wọnyi wa ni orílẹ́ èdè ...
murtala muhammad murtala ramat mohammed tí a bí ní november 8 1938february 13 1976 je olori ijoba nigeria gege bi ologun lati odun 1975 si 1976 igba ti awon ologun egbe re fe gba ijoba ni won pa ogagun obasanjo ti o je igbakeji re ni o bo si ori oye gege olori ijoba lati 1976 si 1979 igbesi aye a bí ògágun murtala rama...
muhammadu buhari nigeria current president muhammadu buhari tí wọ́n bí ní ọjọ́ ketàdínlógún oṣù kejìlá odún 1942 olóṣèlú tí ó jẹ́ ààrẹ orílè-èdè nàíjíríà láàrin ọdún 2015 sí ọdún 2023 ó lo ṣáà àkọ́kọ́ rẹ̀ láàrin odún 2015 sí 2019 àti kejì láàrin ọdún 2019 sí 2023 buhari tí fìgbà kan jẹ́ ogágun méjọ̀ gẹ́nẹ́rà àti pé ó j...
chuba okadigbo chuba okadigbo 17 december 1941 - 25 september 2003 je oloselu omo ile naijiria lati eya igbo ti a bi ni odun 1941 ti o si ku ni odun 2003 okadigbo je aare awon alagba ile igbimo asofin naijiria lati 1999 titi de 2000 itokasi <ns>10</ns> <id>19502</id> <revision> <id>216362</id> <parentid>166404</parenti...
èdè oríṣìíríṣìí àwọn onímọ̀ ní ó ti gbìnyànjú láti fún èdè ní oríkì kan tàbí òmíràn ṣùgbọ́n kí a tó bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn oríkì wònyìí kí èdè túmọ̀ sí èdè níí ṣe pẹ̀lú ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ tí àwọn ènìyàn ń lò ní àwùjọ yálà fún ìpolówó ọjà ìbáraẹni sọ̀rọ̀ ojoojúmó ètò ìdílé tàbí mọ̀lẹ́bí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ gẹ́gẹ́ bí...
merina merina àwọn ti won n so ede wọ̀nyí jẹ́ ará malayo-indonesian wọ́n ní ìtàn tó gbọ̀ọ̀rìn nípa ìsẹ̀dá wọn ati nipa àṣà àtí ètò òsèlú won láàrin orisi awọn ènìyàn madagascar ẹsin kiriyo ati ẹ̀sìn eranko ni wọn ni sìn
mende ede mende jọ ede awọn mande àwọn wọ̀nyí wá lati sudan si apá àríwá eya menda jẹ ẹ̀yà ti o tobi ni afirika wọn lé ni ọ̀kẹ́ méjì
mossi mossi tabi moaaga àwọn ènìyàn mossi jẹ jagunjagun olóyè moro naba ni olórí wọn àwọn tó kọ́kọ́ da mossi àkọ́kọ́ sílẹ̀ wá lati gbana awọn ló tóbi ju ni burkina faso
ngbaka eya ngbaka tabi m'baka je eya eniyan ni orile-ede olominira arin ile afrika awọn wọnyi jẹ awon to ń gbé ìlú ngbaka kò sì sí agbára kan to da wọn pọ ńṣe ni olukuluku n se bi o ti fẹ láàrin ìlú awọn ẹya náà ń gbe ubangi
ìtàn àkọọ́lẹ̀ yorùbá thomas peter taiwo ṣẹ ìtàn bi ede yorùbá ṣe di kíko sí lè yorùbá orthography láti ayébáyé èdè yorùbá wa lábé ìpínsí sòrí tí ọ̀gbẹ́nì thamstrong 1964 se fún àwọn èdè gbogbo èdè yorùbá bọ́ sí abẹ́ ìpín èdè “kwa” èyí sì jẹ́ bẹ́ẹ̀ nítorí pé èdè olóhùn tonalanguage ni yorùbá jẹ́ gẹ́gẹ́ bí a se mọ̀ pé tẹ...
àyàn ayan drummer iṣẹ́ àyàn iṣẹ́ ìlù lílú ni a n pe ni ìṣẹ́ àyàn àwọn ti o n sẹ iṣẹ yii ni a n pe ni “aláyàn tàbí ‘àyàn’ iṣe àtìrandíran ni èyi nitori iṣẹ afilọmọlọwọ ni gbogbo ọmọ ti onílù bá bí sí ìdi àyàn agalú ni o ni láti kọ ìlù lílù paapaa akọbi onílù dandan ni ki àkọ́bí onílù kọ iṣẹ ìlù ko si maa ṣe e nitori àwọ...
ìpèsè ipese drum ìpèsè- ìlù tí àwọn babaláwo ńlù lọjọ ọdún ifá ni ìpèsè awọn mìíran npe e ni ìpẹ̀sì yatọ̀ si ọjọ ọdun ifa a tun nlù ipese lọjọ̀ ti a ba n ṣe isinku tabi ijade oku ọkan nínú àwọn asaaju nibi ifa mẹrin ni ọ̀wọ́ ìlù ti a papọ se ìpèsè- a ìpèsè- ìlù yi funra rẹ lo tóbi jù nínú mẹ́rèẹ̣́rin igi la fi n gbẹ ẹ ...
àgèrè agere drum àgẹ̀rẹ̀- a nlù agẹrẹ lọjọ ọdun awọn ọdẹ idi niyi ti a fi n pe agẹrẹ ni ìlù ogun bi ọlọ́ọ́dẹ tàbí olórí ọdẹ kan bá ku ni a n lù agẹrẹ ọ̀wọ́ ìlù mẹta la papọ̀ se àgẹ̀rẹ̀ ògún a àgẹ̀rẹ̀- eyí ni ìlù to tobi ju pátápátá igi la fi ngbẹ agẹrẹ oju meji ọgbọọgba lo sì nì ìlù yi dabi ìbẹ̀mbẹ́ awọ la fin bòó lójú...
gbẹ̀du pàtàkì ni gbẹ̀du jẹ̀ nínú àwọn ìlù ìbílẹ̀ yorùbá ìlù yii kan naa lawọn kan n pen i àgbà ìyàńgèdè ni ìlẹ̀ yorùbá ìlù mẹta la le tọkasi nínú ọwọ ìlù gbẹ̀du a aféré- ìlù nla ni afẹrẹ ó ga tó iwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà mẹ́rin ó sì gùn gbọọgì géńdé ti ko ba dara rẹ loju ko le gbe nìlẹ oùn rẹ̀ máa n rìnlẹ dòdò ìkeke ni a fi maa ...
ìgbìn ìlù ìgbìn ìlù oriṣà ọbàtálá ni ìlù yii ọjọ̀ àjọ̀dún ọbàtálá ni àwọn olóòṣà yìí ńkó ijó ìgbìn sóde oriṣii ìlù mẹ́rin la le tọ́ka sí lábẹ́ ọ̀wọ́ ìgbìn a ìyá-nlá igi la fi n gbẹ́ ìlù yìí ihò ìnu ìgi naa si dọ́gba jálẹ̀ awọ lafi ńbo oju ìgi ìlù yi lójù kan b ìyá-gan ìlù yii lo tẹle iya-nla òun ló sì dàbí omele tàbí e...
gangan gangan drum gangan ìlù yii lo tẹle kẹrikẹri ó kéré ju àwọn méjèèjì ìsaájú lọ igi la fi ń gbẹ́ òun náà bí i ti àwọn tóókù kò sí ohun ti kẹríkẹrì ní tì gangan ò ní
kànnà-n-gó kanna-n-go drum kànnàngó - igi ti a fi se kànnàngó kéré jù igi ti a fi se ìsaaju ṣùgbọ́n gbogbo ohun ti ìsaájú ni náà ni kannango ni bì a ba tẹ kọ̀ngọ́ bọ kànnàngó o n dun leti kerekere ju ìsaájú
gúdúgúdú gúdúgúdú ìlù yi gan an là bá máa pè ní omele dùndún igi la fi n gbẹ́ ẹ ṣùgbọ́n ojù kansoso lo nì o fi èyí yatọ si awọn bi ìyá-ìlù kẹrikẹri gangan ìsaájú ati kànnàngó ti wọn ni ojù méjìméjì ìlù yìí kò se gbé kọ́ apá bi ti àwọn yòókù ọrùn la máa ń gbé e kọ́ nígbà tí a bá ń lùú bí o ti kéré tó ipa tí ó ń kó nínú ...
àpíntí apinti drum àpíntí ọkan nínú àwọn ìlù ti a nlu nibi aseyẹ ni apinti ẹya ìlù mẹta la papọ ti a n pen i àpíntí a iya-ìlù igi ti a gbẹ ti a si da iho sìnu rẹ la fi nṣe ìya-ìlù oju kan ṣoṣo lo ni oju kan ṣoṣo yi la n fi awọ bo iho ìnu ìgi yi jade si isalẹ rẹ ko si ni awọ iya-ìlù yi ni okun tẹẹrẹ ti a so mọ ara rẹ ok...
ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ohun èlò amúlùúdùn ní ilẹ̀ yorùbá jákè jádò ìlẹ yorùbá la ti ń lù sẹ̀kẹ̀rẹ̀ pàá pàá jùlọ níbí àṣeyẹ oríṣiríṣi sèkèrè jé òkan làra oh un tí ó n mú ìdàgbàsókè àti ìdánilárayá wá fún àwon ènìyàn ní àwùjo sèkèrè yi jé òkan lára ohun ìlù tí wón n lòní apá ìwò oòrùn nd orílè èdè nàìjír...
àpíìrì apiiri àpíìrì tàbí sẹkẹrẹ aré yi wọ́pọ̀ lágbègbẹ̀ èkìtì ó yàtọ̀ sí ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ ti a kọ́kọ̣́ sàlàyé rẹ̀ nítorí pé a kìí lu aro koso àti bẹ̀mbẹ́ síi kìkì ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ là ń lù nìbi ti a ba nsere apíìri orìṣii ṣẹ̀kẹ̣̀rẹ̀ mẹ́ta là ń lù si apiiri a ìya-àjẹ́ àgbe to tobi díẹ̀ la fi n ṣe iya-aje e so igi kan bayi la n ṣe sar...
bwa style=background-color #b0c4de | èdè buamu style=background-color #b0c4de | ẹ̀sìn animism 85<br>christianity 10<br>islam 5 bwa tabi bwaba lọ́pọ̀ je eya kan ni arin ile the places left unconquered were raided by the bamana which led to a weakening of the bwa social and political systems burkina faso ati mali iye àwo...
ṣókúwé ṣókúwé je eya eniyan ni apa arin afrika ìran àwọn tí o ń sọ èdè yìí wá ní orílẹ̀ èdè olómìnira congo àti portuguese àwọn alábàgbéé wọn ni luba-lunda orílẹ̀ èdè angola ni á tí ń sọ èdè yìí iye àwọn ènìyàn tí ó ń sọ èdè yìí jé 455 88 lára ẹbí niger-cong0 ni èdè yìí wa ẹka rẹ si ni bantu
ekeeti ekeeti eket eket- èdè bantu ni èdè yìí gusu ìlà oòrùn orílẹ̀ èdè nigeria ni wọn ti ń sọ èdè yìí ẹya àwọn ti ó ń sọ èdè ibibio ni wọn wọ́ wà ní ìpínlẹ̀ akwa-ibom ni orílẹ̀ èdè nigeria wọn ń sọ èdè yí náà ni benue congo
kongo
èdè bijago èdè bijago tabi bidyogo jẹ́ ọkan pàtàkì lára àwọn orisìírísìí èdè bí i mẹ́ẹ́dógbọ̀n tí wọ́n ń sọ láti ilẹ guinea-bissau orúkọ mìíràn tí a tún mọ èdè yìí sí ni bigogo byougout bijuga budjago bugago bákan náà ni a mò wọ́n mọ àwọn ẹ̀ka èdè bíi anhaki kagbaaga kajoko kamọna àti orango wọ́pọ̀ nínú èdè bidgogo gbo...
bobo madare bobo madare bobo madare èdè yìí jẹ mọ́ èyí tí wọ́n máa ń sọ ní ìwọ̀ oòrùn africa orúkọ mìíràn tí a tún mọ èdè yìí sí ní balck bobo bobo bobo bobo fing àwọn èdè adugbo wọn ni benge bobo dioula bobo jula sogokire sya syabere voré zara ile burkina faso ni wọ́n ti ń sọ ọ́ nígbà tí wọn sijẹ̣ ẹ̀yẹ̀ ti niger-congo...
busoogi busoogi bushoog bushoog bushoog ni a mọ èdè yìí sí bákan náà ni wọ́n tún ń jẹ́ bamong bushong bushongo busoong ganga kuba mbale mongo shongo wọ́n jẹ mọ ẹka èdè ti djeenbe ngende ngombe ngombia ngongo panga pianga shoba shobuia ìsobwa èdè náà tì wà títí dí oni lápá ijọba onimira ilẹ congo bakan náà ni wọ́n jẹ́ ẹ...
ìdomà èdè idoma a lè rí ìdomà ní ààrin gùngùn orílẹ̀ èdè náígíríà àwọn tí wọ́n ń sọ èdè yìí jẹ́ igba méjì ati àádọ́ta ẹgbẹ̀rún àwọn aládùgbóò rẹ̀ ni ibibo igbo mama àti mumuye ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn idoma ni wọ́n jẹ agbẹ wọ́n si máa ń se àpọ́nlé àwọn baba ńlá wọn tí wọ́n ti kú
mumuye mumuye àwọn wọ̀nyí jẹ ara ènìyàn naijiria wọn kere niye wọn si da dúró tẹlẹ ni ipinle taraba ni wọn n gbe ni jalingo wọn le lẹ́gbẹ̀rún lọ́nà irínwó isẹ́ lagalagana ni wọn ń ṣe
àṣà nok àṣà nok yo jade ni arin ile naijiria ni bi odun 1000 sk o si pare lai nidi ni bi odun 200 lk a ko mo ohun ti awon ènìyàn náà pe ara won nitori náà oruko àsà náà ni won fi so ilu won àsà nok wa lati ariwa afrika ni ipinlè niger
èdè ìgbìrà èdè igbìrà tàbí ebira tàbí egbira jẹ́ èdè ní nàìjíríà ní àwọn ìpínlẹ̀ kwárà àti ẹdó àti násáráwá èdè igbìrà èdè yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè naìjírìà àwọn tí wọ́n ń sọ ọ́ jẹ́ mílíọ̀nù kan wọn wà ní àgbègbè èbìrà ní ìpínlè kogi kwara edo àti béè béè lo àwon èka èdè tí ó wà ní abẹ́ rẹ̀ ni okene hima ihima ìgbàr...
ìgbìrà style=background-color #b0c4de | èdè ebira language style=background-color #b0c4de | ẹ̀sìn christianity and islam igbìrà tàbí ebira je eya eniyan ni naijiria èdè yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè náíjíríà àwọn tí wọ́n ń sọ ọ́ jẹ́ mílíọ̀nù kan wọn wà ni àgbègbè ebira ní ìpínlẹ̀ kwara edo okene àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ àwọn ẹ...
igbo e le ka ayoka ni yoruba lori igbo
ibo
èdè ijọ
koin koin èdè koin orúkọ àdúgbò tí wọ́n ń pè é ni itajikan àwọn ènìyàn koin ní wọ́n sì ń sọ ọ́ ó kún fún àlàyé kíkún lórí gírámà èdè ilè cameroon ni wọ́n ti ń sọ ọ́ àwọn ti wọ́n ń sọ èdè yìí jẹ́ àádọ́jọ ẹgbẹ̀rún àwọn mọ̀lẹ́bí èdè koin ni niger-congo atlántic-congo volta-congo àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ
èdè kóngò kikongo tabi ede kongo je ede bantu ti awon eya bakongo ati bandundu n so a èdè tí àwọn ènìyàn wọ̀nyí ń sọ ni kitumba òun ta ń pè ní kongó ní n ǹkan ṣe pẹ̀lú àpapọ̀ àwọn èdè bantu àwọn ibi tí ati n sọ èdè yìí ni angola congo crabon ati zoure ní àarin odún 1960 sí ọdún 1996 àwọn tí ó n sọ èdè yìí dín díẹ̀ ni m...
sínńtààsì èdè aafíríka akande titilayo c sintaasi ede aafirika syntax- john r watters john r watters túmọ̀ sínńtààsì sí bí ìró àti ọ̀rọ̀ se ń so papọ̀ di gbólóhùn àti bí àwọn ìsọ̀rí kọ̀ọ̀kan se hun ara wọn papọ̀ ní ìpele ìpele di gbólóhùn gbogbo èdè ni wọ́n ní ju ọ̀nà kan lọ ti wọn ń gba hun ọ̀rọ̀ wọn tí a bá ń kọ nípa...
zosso ‘zosso’ ‘zosso’ jẹ òrìṣà àdáyé bá tó jẹ pé tí wọ́n bá tí bí ọmọ àjara-tọpá ìyá ọmọ náà kò ní jẹ iyọ̀ títí oṣù afi yọ lókè tí oṣù yìí bá ti yọ wọn á gbé ọmọ náa bọ́ sí ìta láti fi osù han ọmọ náà wí pé kí ọmọ náà wo oṣù tí ó wá sáyé ní ọjọ́ náà ìyá ọmọ náà yòó gbé ọmọ náà bó sí ìta láìwọ aṣo àti ọmọ náà pàápàá tí ...
zangbetọ zangbeto jẹ́ òrìṣà àwọn ẹ̀yà ògù ní àgbádárìgì tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí badagry tí wọ́n gbàgbọ́ pé ìran yorùbá ṣùgbọ́n tí wọ́n ṣẹ̀ wá láti orílẹ̀ èdè olómìnira benin àti orílẹ̀-èdè togo zángbétọ́ lè jade nígbà kúgbàà tí wọ́n bá fẹ́ ṣe ọdún òrìsà tàbí aỵẹyẹ ìbílẹ̀ ‘zangbetọ’ jẹ́ òrìsà tó mò n pa idán ní ọjọ́ ayẹ...
ìrìnàjò lọ sínú òṣùpá ìdòwú oluwaseun adẹ́sayọ̀ ìrìnàjò lọ sínú òṣùpá osupa aye mẹ́jọ míràn bíi’rú ti wa lo n yi po káàkiri òòrùn àwa la ṣìkẹta táa jìnà sóòrùn awọn méjì wà níwájú àwọn mẹ́fà wà lẹ́yìn wa mo ni òòrùn tí à ń wò lókè taa rò pé ó kéré mo ló tóbi lọ́pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà ju gbogbo ilé ayé lọ báyé yìí ṣẹ́ ń yípo òòr...
andora
ijo jesu l’otito
baṣọ̀run gáà baṣọ̀run gáà jẹ́ ìwé ìtàn eré-oníṣe tí gbajúmọ̀ oǹkọ̀wé nì adébáyọ̀ fàlétí kọ ó dá lórí ìtàn olóyè baṣọ̀run tí ìlú ọ̀yọ́ tí wọ́n ń pè ní baṣọ̀run gáà ó jẹ́ afọbajẹ ní ìlú ọ̀yọ́ láyé àtijó kókó inú ìwé ìtàn eré oníṣe yìí ni wípé kí a má ṣe ìkà ìjìnlẹ̀ èdè yorùbá ni ònkọ̀wé náà fi kọ ìwé náà tí ó sì gbé ìtàn...
nàìjíríà nàìjíríà <ns>10</ns> <id>16731</id> <redirect title=àdàkọpron-en /> <revision> <id>68360</id> <timestamp>2009-12-25t192644z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <comment>redirected page to </comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> orílẹ̀-èdè nàì...
tutsi tutsi jé eya kan lárà àwon olùgbé mẹta àwọn ènìyàn orílẹ̀ èdè rwanda and burundi ni apa arin afrika ìyàtọ̀ díẹ̀ ló wà láàrìn àsà àwọn ará tutsi àti hutu àgbẹ̀ àti olùsìn maalu ni isẹ́ àárò abínibí àwọn ara tutsi maálù jẹ́ ohun tí àwọn ará tutsi fi máa ń fi agbára àti ọlà wọn han èyí ló sì mú àwọn ará tutsi jẹ́ ol...
twa twa tabi batwa jé àwon èyà ènìyàn kúkuru pigmy tí a le pè ní àràrá àwọn ni olùgbé tí a ní àkọsílẹ̀ pé ó pẹ́ jù ní àarin gbùngbùn ìlẹ afíríka nibi tí a ti rí àwọn orílẹ̀-èdè bí rwanda burunidi ati ilẹ̀ olomìnira ti congo lóde òní àwọn ará hutu tó sẹ̀ wá láti àwọn ara bantu jọba lé twa lori nígbà tí wọ́n dé agbègbè n...
èdè wolof ede wolof jẹ èdè tí à ń sọ ni atí bèbè senegal mílíọ̀nù méjì-àbọ̀ niye àwọn tó ń sọ awọn olùbágbè wọn ni mandika ati fulaní awọn isẹ́ ọna wọn màa ń rewà tó sì ma ń ní àmìn àti àwòràn àwọn asáájú nínú ẹ̀sìn musulumi ìtan wolof ti wà láti bí ẹgbẹ̀rún ọdún méjìlá tàbí métàlá sẹ́yìn ìtàn ẹbí alátẹnudẹ́nu wọn sọ p...
woyo woyo ní agbègbè congo zaire ni a tin í àwọn ẹ̀yàn woyo a kò le sọ pàtó iye àwọn tó ń gbé agbègbè yìí kiwoyo bantu ni èdè àwọn ẹ̀yà yìí solongo kongo vili àti yombe jẹ́ àwọn olùbágbé ní ñǹkan ẹgbẹ̀rún ọdún kẹ̀ẹdógún prior 15th century ìtàn se akọ̀sílẹ rẹ pe ọmọọba bìnrin nwe kò àwọn ènìyàn rẹ tọ́ yẹ kan dí woyo sod...
wum wum je ilu ni kamẹroon apa ariwa cameroon ni ibùgbé àwọn ènìyàn wum wọ́n jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìlá ènìyàn níye àwọn alábágbé wọn ni esu kom àti bafut èdè wum macro-bantu ni wọ́n n sọ nítori ìgbàgbọ̀ wọn nipa orí kò fẹ̣́si nínú isẹ́ ọnà wọn tí a kì í rì àwòrán ori àgbè ọlọ́gìn àgbàdo isu ati ewébe ni àwọn ará wum wọn tún ...
yaka yaka ní gúsu apa iwo oòrùn congo ti zaire àti ní angola ni àwon ènìyàn yaka wà òké méjìdínlógún 300000 ni wón tó níye lára àwon aládúgbò won ni suku teke àti nkanu’ itan àtenudénu fìdí rè múlè pé àwon ènìyàn yaka pèlú suku jé ara àwon tí ó kógun ja ìlú ńlá kongo ni egbèrún odún kerìndínlógún suku ti je òkan lára k...