raw_text
stringlengths
2
128k
yorùbá yorùbá lè tọ́ka sí
zulu style=background-color #b0c4de | èdè zulumany also speak english afrikaans portuguese or other indigenous languages such as xhosa style=background-color #b0c4de | ẹ̀sìn christian african traditional religion style=background-color #b0c4de | ẹ̀yà abínibí bíbátan bantu · nguni · basotho · xhosa · swazi · matabele · ...
ilẹ̀ yorùbá ilẹ̀ yorùbá ni agbègbè ìgbéró àsà ilẹ̀ àwọn ọmọ yorùbá ní ìwọ̀òrùn áfríkà ilẹ̀ yorùbá fẹ̀ láti nàìjíríà benin títídé togo agbègbè ilẹ̀ yorùbá fẹ̀ tó 142114 km2 106016 km2 inú rẹ̀ 746 bọ́sí nàìjíríà 189 bósí orílẹ̀-èdè benin àti 65 yìókù bósí orílẹ̀-èdè togo ilẹ̀ ìgbéró àsà yorùbá yìí ní iye àwọn ènìyàn bíi ...
orílẹ̀-èdè yorùbá orílẹ̀-èdè yorùbá ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà àwọn ènìyàn yorùbá wà káàkiri ìpínlẹ̀ bí i mẹ́sàn-án àwọn ìpínlẹ̀ náà ni ẹdó èkó èkìtí kogí kúwárà ògùn òndò ọ̀ṣun àti ọ̀yọ́ lóde òní yorùbá wà káàkiri ilẹ̀ àwọn aláwọ̀ dúdú áfíríkà amẹ́ríkà àti káàkiri àwọn erékùsù tí ó yí òkun àtìlántíìkì ká ní ilẹ̀ aláwọ̀ dú...
ìfitónilétí informatics ifitonileti owolabani james ahisu ati akindipe oluwabunmi tope ètò gírámà ìfáàrà “ní àtètèkọ́sẹ ni ọ̀rọ̀ wà …” jọ́ọ̀nù 11 kì í ṣe ohun tó dájú ni pé akẹ́kọ̀ó èdè kọ̀ọ̀kan yóò jiyàn pé ọ̀rọ̀ ni wúnrèn ìpìlẹ̣̀ fún ìtúpalẹ̀ nínú àwọn gírámà a lè yígbà yígbà kí a wádìí lítítésọ̀ fún àríyànjiyàn lórí...
ẹ̀kó ìjìnlẹ̀ nípa ìfitónilétí owolabani james ahisu ẹ̀kó ìjìnlẹ̀ nípa ìfitónilétí informatics ẹ̀kó ìjìnlẹ̀ nípa ìfitónilétí n kọ́ nípa ètò ìṣesí àti ìbáṣepọ̀ àwọn ìlànà adánidá àti ìfi-ọgbọ́n-se tó n pamọ́ tó sì n ṣe ìyípàdà àti ìkójọ ìfitónilétí bákan náà ní ó n sẹ̀dá àwọn ìpìnlẹ̀ ajẹmérò àti tíórì tirẹ láti ìgbà tí à...
omo yoruba
ìmọ̀ ẹ̀rọ sàláwù ìdáyàt olúwakẹ́mi ìmọ̀ ẹ̀rọ bí a bá ń sọ̀rọ̀ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ bí akò bá sọ̀rọ̀ nípa ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì a jẹ́ pé à ń rólé apá kan nìyẹn báwo ni a ó ò ṣe pé orí ajá tí a kò níí pe orí ìkòkò tí a fi ṣè é ìmọ̀ sáyáǹsì ló bí ìmọ̀ ẹ̀rọ sáyáǹsì ni yóò pèsè irinsé tí ìmọ̀ ẹ̀rọ máa lo láti fi se agbára ọ̀nà méjì ló yẹ...
oduduwa odùduwà jẹ́ aláṣẹ àti olùdarí ìran yorùbá òun tún ni gbòngbò kan pàtàkì tí ó so ilẹ̀ yorùbá ró láti ife títí dé ibi k'íbi tí wọ́n bá ti ń jẹ ọba káàkàkiri ilẹ̀ káàrọ̀ -oò -jíire pátá lára ìtàn tó fẹsẹ̀ odùduwà múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí akọni ìgbà ìwáṣẹ̀ nílẹ̀ yorùbá sọ wípé ó jẹ́ ọmọ ọba ti ilẹ̀ lárúbáwá tí wọ́n f'ogun l...
ojú tí ifá fi n wọ́ obìnrin ifá jẹ òrìṣà kan pàtàkì láàárín àwọn yorùbá àwọn yorúbà gbàgbọ́ wípé olodumare lo ran ifá wa láti ode ọrun láti wa fi ọgbọ́n rẹ̀ tún ilé ayé se ọgbọ́n ìmọ̀ àti òye tí olódùmarè fi fún ifá ló fun ifá ní ipò ńlá láàárín àwọn ìbọ ilẹ yorùbá …”a kéré-finú-sọgbọ́n”ni oríki ifá eleyi lo fi han wa ...
ìṣírò isiro awoyemi jolaoluwa awóyẹmí jọláolúwa ìṣirò àwọn yorùbá ní ọ̀nà tí wọn ń gbà ṣe ìsirọ̀ bẹ́ẹ̀ ní àti ọmọkékeré ní àwọn yorùbá ti ń kọ́ ọmọ wọn ni ìṣirò ní ṣíṣe wọn yóò ni kí ó máa fi ení èjì kọrin ṣere bíi ení bí ení ni ọmọde ńkawó èjì bí èjì ni àgbàlà ń tayò ẹ̀ta bi ẹta ẹ jẹ́ ka tárawa lọ́rẹ ayò tí ta náà tún...
ìkọ́ni gbadamosi temitope thomas kíní a mọ̀ sí ìkọ́ni ìkọ́ni túmọ̀ si ìlànà ti àhún gbà láti fii òye hàn láti ìran kan dé òmíràn àti láti ènìyàn sí elòmíràn ní ìdàkejì ẹ̀wẹ̀ ìkọ́ni lèè túmọ̀ sí ìbáwí tàbí ìtọ́sọ́nà láti ọ̀dọ̀ ẹnití ó ju ẹni lọ àmọ́ ki a máa fi ọ̀pá pọ̀ọ̀lọ̀pọọlọ pa ejò ìkọ́n tòní dá lórí ti òye ìmọ̀ tà...
ilesha
orílẹ̀-èdè yorùbá àkàndé saheed adébísí orílẹ̀-èdè yorùbá yorùbá gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀-èdè jẹ́ àti-ìran-díran odùduà pẹ̀lú gbogbo àwọn tí wọn ń sin ọlọrun ni ọ̀nà ti odùduà ń gbà sìn-ín ti wọn si bá a jade kúrò ni agbedegbede ìwọ̀ oòrùn nígbà tí ìrúkèrúdò dé nipa ìgbàgbọ́ rẹ̀ yìí akikanjú yii pinnu láti lọ tẹ orílẹ̀ èdè mir...
buhari
ogun àgbáyé kìíní ìjà ogun àgbayé kìíní láti ọjọ́ ti aláyé ti dáyé ni àwọn ìwọ̀ búburú bí i jàgídíjàgan wàhálà rúkèrúdò ti wà nínú ìgbésí ayé ọmọ ènìyàn rògbòdìyàn kò yé sẹlẹ̀ bẹ́ẹ̀ nì làásìgbò kò roko ìgbàgbé ìdàrúdàpọ̀ nínú ẹbí àríyànjiyàn láàárin ọ̀rẹ́ gbọ́nmisi omi ò to kò yé wáyé láàárín ìlú sí ilu abúléko sí abúl...
esin igbagbo
wikipéédíà
ìyísódì nínú ẹ̀ka-èdè ìkálẹ̀ ìyísódì nínú ẹ̀ka-èdè ìkálẹ̀ ìfáàrà gẹ́gẹ́ bí ìyísódì ṣe ń jẹ yọ nínu ya ìkálẹ̀ tíí ṣe ọ̀kan lára àwọn èka-ède yorùbá máa ń ṣe àmúlò oríṣiríṣi wúnrẹ̀n láti fi ìyísódì hàn ìyísódì lè jẹ yọ nínú ẹyọ ọ̀rọ̀ kan ó sì tún lè jẹ yọ nínu ìhun gbólóhùn kan ṣíṣe àfihàn àwọn ọ̀nà lóríṣiríṣi tí ìyísódì...
ìmò ìṣírò oju ewe imo isiro ìmọ̀ ìsirì je eyi t'on je mo nipa ọ̀pọ̀iye quantity nipa òpó structure nipa iyipada change ati nipa ààyè space idagbasoke imo isiro wa nipa lilo àfòyemọ̀ọ́ abstraction ati ọgọ́bn ìrọ̀nú pelu onka isesiro wiwon ati nipa fi fi eto s'agbeyewo bi awon ohun se ri shapes ati bi won se n gbera moti...
ìmò ìṣirò oju ewe imo isiro ìmọ̀ ìsirò jẹ́ èyí t'on jẹ mo nipa ọ̀pọ̀iye quantity nipa òpó structure nipa iyipada change ati nipa ààyè space idagbasoke imo isiro wa nipa lilo àfòyemọ̀ọ́ abstraction ati ọgbọ́n ìrọ̀nú pelu onka isesiro wíwọ̀n ati nipa fi fi eto s'agbeyewo bi awon ohun se ri shapes ati bi won se n gbera mo...
ọbáfẹ́mi awólọ́wọ̀ jeremiah obáfẹ́mi awólọ́wọ̀ tí a bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹta ẹrẹ́nà ọdún 1909 ti o sí ku lọjọ́ kẹ́sàn-án oṣù karùn-ún èbìbí ọdún 1987 jẹ́ olósèlú ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà láti ẹ̀yà yorùbá awólọ́wọ̀ jẹ́ olórí fún àwọn ọmọ ilẹ̀ yorùbá àti ọ̀kan nínú àwọn olóṣèlú pàtàkì ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà ìgbà èwe a bí ...
àwọn ìpínlẹ̀ nàìjíríà awon ìpínlẹ̀ orile ede naijiria je merindinlogoji36 agbegbe
awon nomba akoko
28 march 27 march | 28 march | 29 march <ns>10</ns> <id>10812</id> <revision> <id>538182</id> <parentid>122275</parentid> <timestamp>2020-07-24t112709z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <minor /> <comment>dáàbò bòó àtúnṣe=gba àwọn alámùójútó nìkan láyè kòdájú ìyípò=gba àwọ...
àwọn àdúgbò ìlú àkúrẹ́ 1 àdégbọlá - ó jẹ́ ibi tí àwọn ọlọ́lá má gbé jù ní ayé àtijọ́ ó sí tún jẹ́ orúkọ ènìyàn 2 ìkóyí - ó jẹ́ ibi tí wọn ti má kó àwọn ìkó jo sí 3 ayédùn - itúmọ̀ rẹ nipé ó jẹ́ orúkọ akọni kan ní ìlú ẹni yìí ní ó má jagun fún nígbà náà 4 òkè àró- jẹ́ àwọn àdúgbò tí má sé ayẹyẹ ọdún bí égún àti bẹ́ẹ̀ lọ...
àdúgbò oyé-èkìtì 1 ijisẹ- àdúgbò ti a n pen i ijisẹ ni o fẹ ilu ọye do lati ile ifẹ wa wọn pa erin ibi ti ẹrin náà ku si iba ni wọn pe ni atẹba ẹni to pa erin náà ni ọlọta aburo ijise ibi ti wọn pa erin náà si ni wọn pe ni ijisẹ ijisẹ lo pa àwọn ara ọyẹ wa lati ile ifẹ pe wọn ti ri ibi tí wọn magbe ijisẹ ni orisu ilu ọ...
àdúgbò àgọ́-ìwòyè 1 ìsámùró- babaláwo kan wà ní àdúgbò yì tí orúkọ rẹ ń jẹ́ ìsà ó má rń gba àwọn àbíkú ọmọ o máa ń mú wọn dúró láti má lè jẹ́ kí wọ́n kú orúkọ bàbá yì ni wọ́n fi wá ń pé àdúgbó yí ní ìsámùró 2 ìdóbì- a má ń ta ọbà ní àdúgbò yí ìdí nìyí tí wọ́n fi ún pè ní ìdóbì 3 àyégbàmí- ọmọ ọkùnrin kan tí ó kọ́kọ́ dé...
29 march 28 march | 29 march | 30 march <ns>10</ns> <id>10812</id> <revision> <id>538182</id> <parentid>122275</parentid> <timestamp>2020-07-24t112709z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <minor /> <comment>dáàbò bòó àtúnṣe=gba àwọn alámùójútó nìkan láyè kòdájú ìyípò=gba àwọ...
31 march 30 march | 31 march | 1 april <ns>10</ns> <id>10812</id> <revision> <id>538182</id> <parentid>122275</parentid> <timestamp>2020-07-24t112709z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <minor /> <comment>dáàbò bòó àtúnṣe=gba àwọn alámùójútó nìkan láyè kòdájú ìyípò=gba àwọn...
1 april 31 march | 1 april | 2 april <ns>10</ns> <id>10812</id> <revision> <id>538182</id> <parentid>122275</parentid> <timestamp>2020-07-24t112709z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <minor /> <comment>dáàbò bòó àtúnṣe=gba àwọn alámùójútó nìkan láyè kòdájú ìyípò=gba àwọn a...
oṣù kẹrin osù kerin odun ni april je ọgbọ̀n ọjọ́ ni o wa ninu osu april
oṣù ṣẹ̀rẹ́ oṣù ṣẹ̀rẹ́ tàbí oṣù kìíní jẹ́ oṣù àkọ́kọ́ nínú kàlẹ́ńdà gregory ọjọ́ mọ́kànlélọ́gbọ̀n ni ó wà nínú osù yìí ọjọ́ kìíní ti oṣù ṣẹ̀rẹ́ ni a ṣe ayẹyẹ ọdún títun ní ìpíndọ́gba oṣù yìí sì jẹ́ oṣù tí ó máa ń tutú jù lọ ní ìdajì ayé àríwá nítorí pé ó jẹ́ oṣù kejì ti ìgbà òtútù níbẹ̀ ó sì jẹ́ oṣù tí ooru máa ń mú jù ...
oṣù kejì osù keji ni february je ninu kalenda gregory ojo mejidinlogbon tabi mokandinlogbon ni o wa ninu february
oṣù kẹta osù keta tí àwọn yorùbá mọ̀ sí oṣù ẹrẹ̀nà jẹ́ oṣù kẹta odun kalenda gìrẹ́górì àti julian ọjọ́ mokanlelogbon ni o wa ninu oṣù ẹrẹ̀nà òun ni oṣù kẹ́jì nínú àwọn oṣù méje tí ó ní ọjọ́ mókanlélogún
oṣù kàrún osù karun ni may je ninu kalenda gregory ojo mokanlelogbon ni o wa ninu osu may
abubakar tafawa balewa abubakar tafawa balewa december 1912 january 15 1966 je omo orile ede nàìjíríà lati apa ariwa ile nàìjíríà balewa je alakoso agba prime minister akoko fun ile nàìjíríà ni igba oselu akoko ile nàìjíríà leyin igba ti nàìjíríà gba ominira ni odun 1960 eni ayesi ni kariaye o gba owo ni orile afrika g...
oṣù kẹfà osu kefa ni june je ninu odun ogbon ojo ni o wa ninu osu june
oṣù keje osu keje ni july je ninu odun ojo mokanlelogbon ni o wa ninu osu july
oṣù kẹjọ osù kẹjọ ni august jẹ́ nínú ọdún ọjọ́ mọ́kànlélógbọ̀n ni ó wà nínú osù august
oṣù kẹ̀sán osù kẹsàán ni september jẹ́ nínú kàlẹ́ndà gregory ọgbọ̀n ọjọ́ ni ó wà nínú osù september
oṣù ọwàrà osù kewa ni october je ninu kalenda gregory ojo mokanlelogbon ni o wa ninu osu october
oṣù kọkànlá osù kokanla ni november je ninu kalenda gregory ogbon ojo ni o wa ninu osu november
oṣù kejìlá osù ọ̀pẹ nínú ònkà oṣù ojú ọ̀run yorùbá ni ó jẹ́ oṣù kejìlá nínú ònkà oṣù ojú ọ̀run ti àwọn gẹ̀ẹ́sì tí wọ́n pè ní december ọjọ́ mọ́kànlélọ́gbọ̀n ni ó wà nínú oṣù yí osù december ni awọn gẹ̀ẹ́sì fa orúkọ rẹ̀ yọ látara ọ̀rọ̀ decem tí ó túmọ̀ sí ten nítorí wípé òun gaan ni oṣù kẹwàá ọdún nínú kalẹ̀dà tí àwọn ca...
nọ́mbà àkọ́kọ́ ninu ìmọ̀ ìṣirò nọ́mbà àkọ́kọ́ prime numbers ni a si àwọn nomba adabaye natural numbers tí wọn ní nọmba ádábá méjí péreé tí a lè fí pín wọn dọ́gba éyí ní nọmbaa 1 atí nọmba ákọkọ fún árá rẹ áwọn nọmba ákọkọ pọ tó bẹẹ tó fí jẹ wípé wọn kò lòpin gẹgẹe bí efklidi ṣé fihàn ní ọdúnn 300 kj kia to bi jesu kj n...
nọ́mbà àdábáyé nínú mathematiki àwon nọ́mbà àdábáyé tàbí nọ́mbà àdábá natural number lé jé òkan nínú àkójopò {1 2 3} èyun nọ́mbà odidi rere tàbí òkan nínú àkójopò {0 1 2 3 } èyun gbogbo nọ́mbà tí kí se tí òdì a n ló nọ́mbà àdàbà fún kíkà ọsàn mefa lowa ninu apẹ̀rè yị bé ni á sí tún n ló won fún sisé ètò elésèsè ipo kej...
mathimátíkì mathematiki tabi ìmọ̀ ìsirò jẹ́ èyí t'on jẹ mo nipa ọ̀pọ̀iye quantity nipa òpó structure nipa iyipada change ati nipa ààyè space idagbasoke imo isiro wa nipa lilo àfòyemọ̀ọ́ abstraction ati ọgbọ́n ìrọ̀nú pelu onka isesiro wíwọ̀n ati nipa fi fi eto s'agbeyewo bi awon ohun se ri shapes ati bi won se n gbera m...
nọ́mbà adọ́gba àti aṣẹ́kù ninu imo mathematiki gbogbo nọ́mbà odidi le je nomba adogba even number tabi nomba aseku odd number lona yi ti o ba je odidi nomba ni opolopo meji nomba na je nomba adogba bibeko yio je nomba aseku fun apere 4 0 8 16 je nomba adogba bee si ni 1 3 7 9 11 je nomba aseku akojopo awon nomba adogba...
nọ́mbà odidi nomba odidi integer je gbogbo awon nọ́mbà àdábáyé alapaotun {1 2 3} ati ti awon alapaosi won −1 −2 −3 pelu nomba òdo ami ti a fi n tokasi akojopo awon nomba odidi ni z tabi formula_1 tabi unicode ℤ ti o duro fun zahlen ti o tumosi nomba ni ede germani
àwọn ọba ilẹ̀ yorùbá onjo ti okeho deji ti ilu akure
bọ́lá ìgè james ajibọ́lá adégòkè ìgè september 13 1930 - december 23 2001 jẹ́ ọmọ yorùbá agbẹjọ́rò ati olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà ní apá ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ nàìjíríà a bí ìgè ní ọjọ́ kẹtàlá oṣu kẹsàán ọdún 1930 ó di olóògbé ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣu kejìlá ọdún 2001 ìgè di alákòóso mínísítà ìjọba àpapọ̀ fún ẹ̀ka ètò ìdá...
wọlé sóyinká akínwándé olúwọlé babátúndé ṣóyínká ọjọ́ìbí 13 july 1934 jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n professor nínú ìmọ̀ lítíréṣọ̀ literature alákọsílẹ̀ eré orí ìtàgé playwright àti akéwì poet wọlé sóyinká jẹ́ ògidì ọmọ yorùbá lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ó gba ẹ̀bùn nobel ní ọdún 1986 fún iṣẹ́ ọwọ́ ọ rẹ̀ lórí i ìgbéga ìmọ̀ ìkọ̀wé ìgbà èwe àt...
chinua achebe chinua achebe oruko abiso albert chinualumogu achebe 16 november 1930 21 march 2013 jẹ́ ọmọ orile ede naijiria lati eya igbo ni apa ila oorun naijiria ojogbon ninu imo ikowe literature ni achebe je opo ni ile afrika ni won si mo achebe gege bi okan ninu awon omowe intellectual pataki ti a jade ni ile afri...
nọ́mbà gidi nínú ìmọ̀ ìṣirò nọ́mbà gidi real number ni a mọ̀ sí àwọn nọ́mbà tí a ko lè gé gẹ́gẹ́ bí nọ́mbà oníyemẹ́wàá decimals tí kò lópin fún àpẹẹrẹ 24871773339… àwọn nọ́mbà gidi jẹ́ nọ́mbà oníìpín nọ́mbà bí 42 àti −23/129 àti nọ́mbà aláìníìpín nọ́mbà gbòngbò alágbára-méjì 2 square root tí wọ́n sì ṣeé fihàn gẹ́gẹ́ bí...
àwọn ẹ̀ka-èdè yorùbá awon eka-ede yoruba tèmítọ́pẹ́ olúmúyìwá 1994 àwọn ẹ̀ka-èdè yorùbá 1akúrẹ́ ìbàdàn montem paperbacks isbn 978-3297-3-3 ojú-ìwé = 58 ọ̀rọ̀-ìṣáájú èdè yorùbá àjùmọ̀lò ni ó pa gbogbo ẹ̀yà yorùbá pọ ṣùgbọ́n ẹ̀ka-èdè tí ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan ń sọ yàtọ̀ láti ilú kan sí èkeji ìyàtọ́ yìí le hàn ketekete tàbí kí ó f...
ilu ijebu-jesa
ìsèdálẹ̀ ìlú ìjẹ̀bú-jẹ̀ṣà ìtàn ìsèdálẹ̀ ìlú ìjẹ̀lú-jèsà oríṣìíríṣìí ìtàn àtẹnudẹ́nu ni a ti gbọ́ nípa ìlú ìjẹ̀bú-jẹ̀ṣà ọ̀rọ̀ òkèèrè sì nìyí bí kò bá lé yóò dín ọ̀kan nínú àwọn ìtàn náà sọ pé ọwà iléṣà kìíní ajíbógun àti ọba ìjẹ̀bú - jẹ̀ṣà kìíni agígírí jẹ́ tẹ̀gbọ́n tàbúrò ọba ìjẹ̀bú - jẹ̀ṣà ni ẹ̀gbọ́n tí ọwá sì jẹ́ àbú...
àgàdá ní ìlú ìjẹ̀bú-jẹ̀ṣà ìtàn bí àgàdá ṣendé ìlú ìjẹ̀bú-jẹ̀ṣà ìtàn méjì ló rọ̀ mọ́ bi àgàdá ṣe dé ìjẹ̀bú-jẹ̀ṣà ìtàn kìíní sọ fún wa pé ìlú ìlayè ni wọ́n tí gbé e wá sí ìjẹ̀bú - jẹ̀ṣà ìlú ìlayè yí ti wà lásìkò kan ní ayé àtijọ́ ṣùgbọ́n ìwádìí fi hàn wá pé kò sí i mọ́ lóde òní ìtàn sọ pé ọba ìjẹ̀bú -jẹ̀ṣà jẹ́ jagunjagun...
egbe omo oduduwa
samuel ladoke akintola samuel ladoke akintola july 6 1906 - january 15 1966 je oloselu omo orile ede naijiria lati eya yoruba ni apa ila oorun a bi ni ojo kefa osu keje odun 1906 ni ilu ogbomosho ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí sámúẹ̀lì sínú ìdílé akíntọ̀lá ní ìlú ògbómọ̀ṣọ́ bàbá rẹ̀ ni akíntọ̀lá akínbọ́lá nígba tí ìyá rẹ̀ ń j...
nọ́mbà oníìpín ninu imo mathematiki nomba oniipin rational number ni nomba ti a le ko le gege be ipin nọ́mbà odidi meji nomba bi formula_1 to je pe b ki se odo a le ko awon nomba oniipin ni opolopo ona fun apere formula_2 sugbon o d'ero julo nigbati a ati b ko ba ni nomba kanna ti a le fi pin won a fi 1
vfd microfinance bank vfd microfinance bank jẹ́ báǹkì oní nọ́ḿbà ni kikun pẹlu olu ni ipinle eko naijiria gẹgẹbi banki oni nọmba o funni ni awọn iṣẹ ifowopamọ ọfẹ si awọn ọmọ orilẹ-ede naijiria gbenga omolokun ni olori banki naa gẹgẹbi oludari alakoso vfd microfinance bank jẹ oniranlọwọ ti ẹgbẹ vfd ile-iṣẹ idoko-owo oh...
jaiz bank commercial institute in nigeriajaiz bank plc ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn bánkìì tí ó ń ṣiṣẹ́ lábẹ́ bánkìì ìsìlámù tí kò rọ̀gbọ̀kú lé ìjọba ó jẹ́ bánkíì àkọ́kọ́ fún ìdínwó ní orílé-èdè nigeria tí olú ìyá ilé iṣẹ́ wọn wà ní abuja olú ìlú nigeria ní december ọdún 2012 bánkíì yìí jẹ́ elétò ìsúná alábọ́dé ní nigeria ní ...
citibank citibank na na dúró fún “ association orilẹ-ede ” jẹ́ onírànlọ́wọ́ ilé-ìfowópamọ́ améríkà àkọ́kọ́ tí àwọn iṣẹ́ ìnáwó ti ìlú ìlú citigroup citybank tí a dá ní 1812 bí city bank of new york àti kí ó tó di first national city bank of new york báńǹkì náà ní àwọn ẹ̀ka 2649 ní àwọn orílẹ̀-èdè 19 pẹ̀lú àwọn ẹ̀ka 723 ...
heritage banking company limited nigerian financial services institutionheritage bank plc tí a tún n pè ní heritage bank jé̩ ilé ìfowopamọ o jẹ ọkan lara awọn ile ifowopamọ ti gbogbo-gbo ti ile ifowopamọ apapọ ti naijiria fi ọwọ si tii ṣe akoso ọrọ ifowopamọ ni naijiria pẹlu aṣẹ iṣiṣẹ lati ṣe iduna dura eto ifowopamọ e...
stanbic ibtc holdings stanbic ibtc holdings ti gbogbo aye mo si stanbic ibtc ile-ise ti o pese eto owo ati inowo ni orile ede naijiria olu ilese ibtc wa ni walter carrington crescent victoria island lagos stanbic ibtc holdings wa lara standard bank groupileese isuwo nla ti o kale si orile-ede south africa standard bank...
moniepoint microfinance bank moniepoint inc tí a mọ tẹ́lẹ̀ sí teamapt inc jẹ́ ilé-iṣẹ fintech tí tosin eniolorunda jẹ́ oludasilẹ iléṣẹ náà ní ọdún 2015 tí o dálé lórí wí wá ọ̀nàbáyọ sí ètò ìsúnná àmì-ẹ̀yẹ moniepoint ti wà lára àwọn ilé-ìfowópamọ́ tó ti lórúkọ lórí ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà lẹ́yìn tí wọ́n da sílẹ̀ ní ọdún ...
guaranty trust bank guaranty trust holding company plc tí a tún mọ̀ sí gtco plc jẹ́ ilé iṣẹ ìfowópamọ́ káàkiri àgbáyé tí ó ń ṣe ìdókòwọ̀ ìṣàkóso owó ìfẹ̀hìntì ìṣàkóso dúkìá àti àwọn iṣẹ́ tó ń rísí owó sísan olú ilé-iṣẹ́ wọ́n wà ní victoria island ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà a dá gtco plc sílẹ̀ ní oṣù keje ọdún 2...
first city monument bank first city monument bank fcmb ẹgbẹ tí fcmb group plc ó jẹ́ ilé ìṣe tí ìnáwó a dání tí headquartered ní lagos fcmb group plc ní ẹ̀ka mẹsan tí a pín wọn sì ìṣe owó mẹ́ta commercial and retail banking investment banking and asset and wealth management ní oṣu december 2020iye tí dúkìá wọ́n ní yé ló...
ecobank nigeria ecobank nigeria limited tí gbogbo ènìyàn mọ̀ dáadáa sí ecobank nigeria jẹ́ báǹkì gbogbogbò ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn báǹkì tó gbàwé àṣẹ lọ́wọ́ báǹkì gbogbo gbò nàìjíríà báǹkì apàṣẹ fún orílẹ̀-èdè ìsọníṣókí báǹkì náà bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ọdún 1989 ó ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi báǹkì àgbáyé nípa pípès...
zenith bank nigerian commercial financial services companyzenith bank plc jẹ́ ẹ̀ka ìfowópamọ ní ìlú nìgíríà àti anglophone apá iwọ̀ oòrùn afíríkà ilé ìfowópamọ àpapọ̀ tí ìlú nìgíríà tí fòǹtẹ̀ lu gẹ́gẹ́ bí ilé ìfowópamọ kéékèèké àjọ fún ètò ìfowópamọ ní ọjọ́ ọ́kànlélọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 2019 ní 161bn ni àkójọpọ̀ ìní ...
first bank of nigeria first bank of nigeria limited jẹ́ ilé-ìfowópamọ́ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti ilé- iṣẹ́ ètò iṣúná ni ìpínlẹ̀ èkó orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ báǹkì àkọ́kọ́ ní ìwọ̀-oòrùn áfíríkà first bank of nigeria limited ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí òbí ilé-iṣẹ́ fún àwọn 'fbn bank ni orílẹ̀-èdè congo ghana gambia guinea sierra-l...
keystone bank limited nigerian commercial bankkeystone bank limitedni ile ifowopamo kan ni nigeria o je lara ile ifowopamo ti o gba iwe ofin lowo ile ifowopamo olu ilu ile nigeria the national banking regulator overview keystone bank ma n fun eto gbigba owo ati ti toju owo fun awón kopirason nla ile-ise ijoba ile-ise k...
kuda bank kudatí a tún mọ̀ sí kuda technologies jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ tó níṣe pẹ̀lú ètò ìṣúná ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti uk babs ogundeyi àti musty mustapha ni ó dáa sílẹ̀ ní ọdún 2019 kuda wà lára ọ̀kan nínú méje àwọn ilé-iṣẹ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ ìbẹ̀rẹ̀pèpẹ̀ áfíríkà wef ní ọdún 2021 iye ìwọ̀n ìfowópamọ́ kuda ni 500 million ó ...
access bank access bank plc tí a mọ̀ sí access bank jẹ́ ilé-ìfowópamọ́ gbogboogbò ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó sì jẹ́ ohun-ìní access bank group ó ní ìwé-àṣẹ nípasẹ̀ central bank of nigeria olùṣàkóso ilé-ìfowópamọ́ orílẹ̀-èdè ní àkọ́kọ́ wọ́n jẹ́ báńkì ilé-iṣẹ́ kan ní ọdún 2012 wọ́n gbòòrò sí báńkì ti ara-ẹni àti ilé-ìfowóp...
unity bank plc unity bank ti a mo si unity bank plc je ile ifowopamo kan ni orike ede naijriaje owo ise nla kan to won se ni orile ede naijiria won wa ni ile eko ni naijriaunity itoju ise kan ni abuja olu-ilu naijiria ni december 2012ile ifowopamo akojopo ohuni wo us245 billion ngn396 billion pelu aeon shareholders' eq...
sterling bank sterling bank plc tó jẹ́ ilé-ifowópamọ́ iṣowo orilẹ-ede ti o ni kikun ti ni iwe-aṣẹ nipasẹ central bank of nigeria lori awọn ebute reuters ati bloomberg o jẹ idanimọ bi sterlnb lg ati sterlnba nl lẹsẹsẹ ilé-ifowópamọ́ máa ń pese àwọn iṣẹ́ sí àwọn ènìyàn kọọkan àwọn iṣowo kékeré smes àti àwọn ilé-iṣẹ́ nlá ...
first lady of nigeria informal title held by the spouse of the president of nigeria arábìnrin ààrẹ orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ àkọ́lé gbẹ̀fẹ̀ ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ àtéwógbà tí ìyàwó ti ààrẹ orílẹ̀-èdè nàìjíríà mú dání ìyàwó ààrẹ lọ́wọ́lọ́wọ́ ni aisha buhari tí ó ti di àkọ́lé náà láti ọjọ́ ọ̀kàn-dín-lọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 20...
audrey ajose nigerian lawyer and writer audrey olatokunbo ajose ọjọ́-ìbí c 1937 jẹ́ àgbẹjọ́rò àti akòwé ọmọ nàìjíríà ó ṣiṣẹ́ bí aṣojú orílẹ̀-èdè rẹ̀ sí scandinavia láti ọdún 1987 sí 1991 ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ ọmọbìnrin ọmọba oladele ajose àti beatrice spencer roberts audrey ajose jẹ́ ọmọ obìnrin ilẹ̀ òkèèrè k...
emily nkanga emily nkanga jẹ́ ayàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti ilẹ̀ọba aṣọ̀kan ó tún ń ṣe fíìmù jáde nkanga gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn olórin bi koker aramide boj olamide jidenna not3s mr eazi mayorkun adekunle gold sarz òṣèré adesola osakalumi agbábọ́ọ̀lù tammy abraham àti femi kuti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àwòrán nk...
lepacious bose bose ogunboye tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gún oṣù kẹrin ọdún 1976 tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ sí lepacious bose jẹ́ aláwadà àti òṣèrébìnrin ní ilé isé nollywood ní ọdún 2014 ó gba àmì-ẹ̀yẹ 2014 golden icons academy movie awards fún eré àwàdà rẹ̀ nínú fíìmù “being mrs elliot”
biola adebayo biola adebayo jẹ́ òṣèrébìnrin tí ó ṣeré nínú àwọn eré bi jade's cross tori owo àti àwọn eré mìíràn òṣèrébìnrin náà eniola badmus àti banky w ṣe ìpòlongo nípa àwọn ọ̀nà láti kọjú ààrùn coronavirus nípa tí ààrùn náà ń jà fitafita ní nàìjíríà wọ́n rọ àwọn ènìyàn láti dúró sínú ilé àti láti lọ àwọn èlò ìfowọ́...
jamilah tangaza jamilah tangaza níkejì jamilah tangaza jẹ́ àkọ̀ròyìn àti ìmọ-ẹ̀rọ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ àkọ̀ròyìn bbc tẹ́lẹ̀ níbi tí ó ti ṣisẹ́ ní onírúurú àwọn ìpò ko tó di olórí hausa service tangaza jẹ́ ẹlẹ́gbẹ́ tí reuters institute fún ikẹ́kọ ti ìwé ìròyìn university of oxford àti ọmọ ẹgbẹ́ ti chatered mana...
toluwani obayan nigerian writer toluwani obayan jẹ́ akọ̀wé ìbojú ara nàìjíríà olókìkí jùlọ fún kíkọ àwọn fíìmù bíi 'ponzi' 'this lady called life' ó tún jẹ́ òǹkọ̀wé ìwé tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ 'becoming a spectacular woman'
tokunbo abiru nigerian politician and banker born 1964mukhail adetokunbo abiru fca tí a bí ní 15th march ọdún 1964 jẹ́ òṣìṣẹ́ báǹkì àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni sẹ́nátọ̀ tó ń sojú àgbègbè senatorial lagos east ní ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ olùdarí àti alákòso àgbà ilé ìfowópamọ́ polaris ...
funke adesiyan funke adesiyan jẹ́ òṣèrébìnrin olóṣèlú àti olùrànlọ́wọ́ aisha buhari ìyàwó ààrẹ orílẹ̀-èdè nàìjíríà lórí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ àṣà àti àwùjọ ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ adesiyan jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ìbàdàn ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ó lọ ilé-ìwé time and tide international school ibadan city academy saint anne's school àti oriwu college...
the 48 laws of power 1998 non-fiction new york times bestseller book by robert greene òfin méjìdínláàádọ́ta agbára' the 48 laws of power 1998 jẹ́ ìwé àpilẹ̀kọ oníṣìípayá tí oǹkọ̀wé america robert greene kọ ọdún 1998 ìwé yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìwé tí new york timee tà wàràwàrà wọ́n ta igba kan lé ní mílíọ̀nù kan ìwé ná...
robert greene american author american author born 1959 robert greene tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrìnlá oṣù karùn-ún ọdún 1959 jẹ́ oǹkọ̀wé ọmọ amẹ́ríkà tí ó kọ ìwé nípa strategy power àti seduction ó ti kọ oríṣiríṣi ìwé tí wọ́n tà wàràwàrà káàkiri àgbáyé lára wọn ni òfin méjìdínláàádọ́ta agbára the art of seduction the 33 stra...
shola adewusi shola adewusi tí a bí ní ọdún 1963 jẹ́ òṣèrébìnrin òṣerébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àpẹrẹ awọn iṣẹ́ rẹ̀ lórí ẹ̀rọ ìmóhùn máwòrán ni little miss jocelyn bbc comedy sketch show series tí jocelyn jee esien kọ òun ni ó ń kó ipa auntie olu lọ́wọ́ lọ́wọ́ nínú fíìmù cbs bob hearts abishola
igbo biseni igbó biseni igbó omi tàbí igbó irà tí ó fìkàlẹ̀ láàárín ìlú ahoada àti apá òkè igbó orashi ní agbègbè niger delta igbó náà tóbi tó ìwọ̀n kìlómítà 219 ní ìbú àti òró tí ó kún fún ilẹ̀ omi àwọn koríko rẹ̀ igbó biseni jẹ́ inú irà tí ó kún fún àwọn igi gẹdú àti àwọn koríko mìíràn tí wọ́n sáàbà máa ń gbẹ lásìkò ...
jaiz
diamond bank plc
sambisa forest sambisa forest jẹ́ igbó kan ní ìpínlẹ̀ bọ̀rnó àríwá apá ìlà oòrùn nàìjíríà ó wà ní gúúsù apá ìwọ oòrùn chad basin national park ó sì tó bí kilometer ọgọ́ta láti gúúsù ìlà-oòrùn maiduguri olú ìlú ìpínlẹ̀ bọ̀rnó ilé sambisa forest tó kilometer èjì dín ní okòó-lé-ní-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta518 ilẹ̀ sambisa sambisa for...
jos plateau jos plateau jẹ́ ilẹ̀ òkè kan tí ó sún mọ́ àárín orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n fún ilẹ̀ náà ní orúkọ rẹ̀ nítorí pé ó wà ní ìpínlẹ̀ plateau àti nítorí jos olú-ìlú ìpínlẹ̀ plateau ilẹ̀ òkè náà jẹ́ ilé fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn pẹ̀lú oríṣi àṣà àti èdè ilẹ̀ jos plateau jos plateau ní ilẹ̀ tí ó tó 8600 km² gígún rẹ̀ ...
charles ndukuba
masoja msiza masoja josiah msiza ti a bi ni oṣu kẹwa 5 1964 jẹ oṣere south africa kan akewi ati akọrin o je olokiki julọ fun iṣafihan “nkunzi mhlongo” ni telenovela uzalo ti o gba ami-eye tete aye wan bi msiza ni kwa-thema ilu kan to wa ni agbegbe south africa ti gauteng ifẹ rẹ fun iṣere bẹrẹ nigbati o jẹ ọmọ ọdun 9 at...
gígé igi lulẹ̀ ní nàìjíríà gígé igi láti ṣe pákó gígé igi lulẹ̀ láti gbin irúgbìn àti gígé igi lulẹ̀ láti fi dánọ́ jẹ́ gbòógì jùlọ nínú àwọn ìdí tí àwọn ènìyàn fi ń gé igi lulẹ̀ ní nàìjíríà láàrín ọdún 2000 sí 2005 nàìjíríà jẹ́ rílẹ̀-èdè tí ó gé igi lulẹ̀ jùlọ ní àgbáyé gẹ́gẹ́ bí àjọ the food and agriculture organizati...
shalewa ashafa shalewa ashafa tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù keje ọdún 1995 tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ sí shallystar jẹ́ òṣèrébìnrin nollywood tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ fún ipa rẹ̀ nínú eré ajoche àti the razz guy ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ shalewa ashafa jẹ́ àbíkẹ́yìn àwọn òbí rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ ogun ó lọ ilé-ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ ní christ the cornerston...
niger delta niger delta jẹ́ ilẹ̀ àti iyẹ̀pẹ̀ tí ó sàn láti odò ọya tí ó sì wà ni gulf of guinea ti atlantic ocean nàìjíríà ó wà lórí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpínlẹ̀ ní nàìjíríà ọ̀pọ̀lopọ̀ lọ ń gbé lórí niger delta ọ̀pọ̀lọpọ̀ sì mọ ibè sí oil rivers nítorí ibè ni wọ́n ti ń ṣe epo pupa ní nàìjíríà ibẹ̀ náà sì jẹ́ ibi tí ọ̀pọ̀lopọ̀ ep...
upper orashi forest reserve upper urashi forest reserve jẹ́ ibi ìpamọ́ ohun àdáyébá ní ìpínlẹ̀ rivers nàìjíríà tí ó wà ní òkè òkè ti odò urashi nítòsí abúlé ikodi ní ahoada west ìfipamọ́ náà ní agbègbè 25165 ha 97163 sq mi ó jẹ́ ìyasọ́tọ̀ ilẹ̀ olómi tí ó ṣe pàtàkì káríayé lábẹ́ àpéjọ ramsar ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹrin ọdú...