raw_text
stringlengths
2
128k
igbó òkè orashi igbó òkè urashi jẹ́ igbó kan lábẹ́ àbò ìjọba ní ìpínlẹ̀ rivers ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà níbi òkè tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ odò urashi ní abúlé ikodi ti ahoada west igbó náà gba ilẹ̀ tí ó tó 25165 ha 97163 sq mi àjọ ramsar convention ká mọ́ àwọn igbó tí ó ti ó ṣe pàtàkì ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 2008 ìgbà ní i...
cross river national park cross river national park jẹ́ pápá ìṣeré kan ní ìpínlẹ̀ cross river nàìjíríà ó pín sí apá méjì apá okwangwo tí wọ́n dá kalẹ̀ ní ọdún 1991 àti apá oban tí wọ́n dá kalẹ̀ ní ọdún 1988 ilẹ̀ rẹ̀ tó 4000 km2 púpọ̀ nínú rẹ̀ sì kún fún igbó pàápàá jùlọ ní àríwá àárín pápá ìṣeré náà àti apá pápá ìṣeré ...
kainji national park kainji national park jẹ́ pápá ìṣeré ní ìpínlẹ̀ niger àti kwara orílẹ̀ èdè nàìjíríà wọ́n da kalẹ̀ ní ọdún 1978 ó gba ilẹ̀ tí ó tó ó pín sí apá mẹ́ta apá ti adágún kainji níbi tí wọn ò ti gba iṣẹ́ apẹja láyè igbó borgu tí ó wà ní apá ìwọ̀ oòrùn adágún náà àti igbó zugurma nítorí àìsí àbò tó péye ni à...
ààlọ́ erinmi ìjàpá àti erin òkè apààlọ́ ààlọ́ o agbe ààlọ ààlọ̀ apààlọ́ ààlọ mi dá lórí ìjàpá tó dá'jà ṣílẹ̀ láárín erin òkè àti erinmi nígbà láíláí erin òkè àti ìjàpá jẹ́ ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ ìjàpá jẹ́ àgbè nígbà tí erin òkè jẹ́ ògbójú ọdẹ apẹran ìjàpá àti erin a máa ṣe pàṣípààrọ oúnjẹ oko bíi iṣu ikàn ẹ̀gẹ́ ṣùgbọ́n kò tẹ...
hilda baci hilda effiong bassey tí ọ̀pọ̀lopọ̀ ènìyàn mọ̀ sí hilda baci a bi ní ọjọ́ ogún oṣù kẹ́sàn-án ọdun 1996 jẹ́ aláṣè àti òṣèrébìnrin ọmọ orilẹ-èdè nàìjíríà ní osù kẹ́jọ ọdún 2021 o jáwé olúborí nínú idije jollof faceoff” ìpìlẹ̀ àti iṣẹ́ rẹ̀ hilda wá láti ìjọba ìbílẹ̀ nsit ubium ìpínlẹ̀ akwa ibom nàìjíríà wọ́n bi ...
diesel locomotive factory marhowrah the diesel locomotive factory marhowrah jẹ́ àpapọ̀ ilé iṣẹ́ ọkọ̀ ojú-irin ti ge ti orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà pẹ̀lú àwọn reluwé ti orílẹ̀-èdè india fún ṣíṣe ọkọ̀ ojú irin tí ìwọ̀n agbára gíga rẹ̀ tó 1000 tí wọ́n rọ fún bíi ọdún mẹ́wàá síwájú si láti ṣiṣẹ́ lórí àwọn òpópónà ojú-irin orílẹ̀-è...
igbó òkè cameroon igbó òkè cameroon jẹ́ àwọn igbó tí ó wà ní àwọn òkè gulf of guinea tí ó sì pàlà láàrin orílẹ̀-èdè cameroon àti nàìjíríà agbègbè ibè kún fún àwọn igi àti koríko àwọn igi ibè ń díkù si àwọn koríko rẹ̀ ń sì pò si nítorí iṣẹ́ àgbẹ̀ tí wọ́n ń ṣe níbẹ̀
igbó òkè cameroonian
kamuku national park kamuku national park jẹ́ ọ̀kan lára àwọn pápá ìṣeré nàìjíríà tí ó wà ní ìpínlẹ̀ kàdúná nàìjíríà pẹ̀lú ilẹ̀ tí ó tó a 1120 km2 nítorí àìsí àbò tí kò péye ní agbègbè náà àjọ pápá ìṣeré fún orílẹ̀ èdè nàìjíríà dáwọ́ iṣẹ́ dúró ní pápá ìṣeré náà àti ní pápá ìṣeré kainji national park àti chad basin nati...
okomu national park okomu national park tí a mọ̀ tẹ́lẹ̀ sí okomu wildlife sanctuary jẹ́ igbó kan tí ó wà ní inú okomu forest reserve ní ìjọba ìbílẹ̀ ovia south-west ti ìpínlẹ̀ ẹdó orílẹ̀ èdè nàìjíríà pápá ìṣeré náà wà fi kìlómítà ọgọ́ta jìnà sí benin city igbó tí ó wà ní ẹgbẹ́ pápá ìṣeré náà jẹ́ ilé fún àwọn oríṣiríṣi ...
old oyo national park egan orile-ede oyo atijọ jẹ ọkan ninu awọn ọgba-itura orilẹ-ede naijiria ti o wa ni iha ariwa ipinle oyo ati gusu ipinle kwara nigeria o duro si ibikan jẹ 2512 km2 ti ilẹ ni ariwa ipinle oyo guusu iwọ-oorun nigeria ni latitude 8° 15' ati 9° 00'n ati longitude 3° 35' ati 4° 42' e ipo naa ti gbe ọgb...
agodi gardens agodi gardens èdè yoruba ọgbà agodi jẹ́ ọgbà kan tí ó wà ní ìlú ìbàdàn orílẹ̀ èdè nàìjíríà àwọn ènìyàn tún mọ̀ ọ́ sí agodi botanical gardens agodi gardens ibadan ọgbà náà gba ilẹ̀ tí ó tó 150 acres ìtàn orúkọ ọgbà náà tẹ́lẹ̀ ni agodi zoological and botanical gardens wọ́n dá agodi gardens kalẹ̀ ní ọdún 196...
àwọn òkè mandara mandara mountains aèdè yoruba àwọn òkè mandara jẹ́ àwọn òkè tí ó wà ní àríwá àlà láàrin cameroon àti nàìjíríà tí ó gùn láti odò benue ní dé àríwá ìwọ̀ oòrùn maroua ní àríwá òkè tí ó ga jù níbẹ̀ ni mount oupay àdúgbò náà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ olùgbé pàápàá jùlọ àwọn tí ó ń sọ èdè chadi pẹ̀lẹ́ pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà mo...
millennium park abuja the millennium park jẹ́ pápá ìṣeré tí ó tóbi jù ní ìlú abuja olú ìlú orilẹ-èdè nàìjíríà ó wà ní agbègbè maitama nínú ìlú náà ọbabìnrin elizabeth kejì ni ó ṣe àfilọ́lẹ̀ pápá ìṣeré náà ní ọjọ́ kẹrin oṣù kejìlá ọdún 2003 ó sún mọ́ ilé ààrẹ orílẹ̀ èdè nàìjíríà odò kan la pápá yìí kọjá ó sì pín sí méjì...
isaac boro park isaac boro park jẹ́ pápá ìṣeré kan tí ó wà ní agbègbè old gra ní olú-ìlú ìpínlẹ̀ rivers port harcourt wọ́n so pápá ìṣeré náà lórúkọ tẹ́lé isaac boro ẹni tí ó jẹ́ ajàfẹ́tọ́ ọmọ ènìyàn ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà ibi tí ó wà ní pàtó ni 4°47'16n 4787960 7°0'19e 7005517 ó wà ní odi kejì mile one ó sì jẹ́ ilé fún...
the ap 42 compilation of air pollutants emission factors the ap 42 compilation of air pollutant emission factorsàtòpọ̀ àwọn ohun ìṣokùnfà ìtúsóde afẹ́fẹ́ ìdọ̀tí náà jẹ́ àwọn àjọ tó ń dáàbò àti mójútó àgbègbè ti orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà epa ìròyìn ohun ìtúsóde lórí ìdọ̀tí afẹ́fẹ́ àtẹ̀jáde àkọ́kọ́ ní ọdún 1968 ítí di 2018 upd...
brila fm brila fm jẹ́ iléṣe igbogunsafefe erẹ idaraya tí wón dá sílè ní ọdún october 1 2002 larry izamoje jẹ́ oludasile iléṣe náà tí ó jẹ iléṣe igbohunasfefe erẹ idaraya àkọ́kọ́ ní orílẹ̀ èdè nigeria brila fm ní iléṣe mẹ́rin ní èkó abuja onitsha àti port harcourt iléṣe náà ṣẹṣẹ ṣe awijare ní kaduna ní ọdún 2014 fifa wo...
fresh fm radio network in nigeria fresh fm jẹ́ nẹ́tíwọkì àwọn ilé-iṣẹ́ rédíò ní nàìjíríà olayinka joel ayefele ló ni í àwọn ìbùdó fresh fm wà ní abẹ́òkuta adó-èkìtì àkúrẹ́ ìbàdàn èkó àti òṣogbo ìtàn ètò bẹ̀rẹ̀ ní ìbàdàn ní ọdún 2015 àti abẹ́òkuta ní ọdún 2018 ìbùdó adó-èkìtì bẹ̀rẹ̀ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ lọ́dún 2020nẹ́tíwọkì ...
ife ìdílé family love jẹ́ nẹtiwọki rédíò aládani kan tí ó ní àwọn ibùdó mẹ́rin ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ohùn ìní nípasẹ multimesh broadcasting company limited àwọn ibùdó wọ́n wà ní ìlú abuja port harcourt enugu ati umuahia multimesh gba ìwé-àṣẹ láti national broadcasting commission láti ní ilé-iṣẹ́ rédíò ni ọdún 20...
cool fm nigeria cool fm nàìjíríà jẹ́ ilé-iṣé rédíò tó ń sọ èdè gẹ̀ẹ́sì ní nàìjíríà pẹ̀lú àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà jákèjádò mẹ́rin nínú àwọn àgbègbè ìgbèríko mẹ́fà ní nàìjíríà o n ṣiṣẹ́ bíi cool tv àti rédíò orí ayélujára ilé -iṣẹ́ rédíò jẹ́ àgbéjáde àti àpáta fún àwọn òǹwòran àgbà ní ọdún 2019 cool fm gbàlejò ifọrọwanilẹnu...
family love family love jẹ́ nẹtiwọki rédíò aládani kan tí ó ní àwọn ibùdó mẹ́rin ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ ohùn ìní nípasẹ multimesh broadcasting company limited àwọn ibùdó wọ́n wà ní ìlú abuja port harcourt enugu ati umuahia multimesh gba ìwé-àṣẹ láti national broadcasting commission láti ní ilé-iṣẹ́ rédíò ni ọdún ...
raypower raypower jẹ ẹgbẹ́ kàn tí àwọn ilé-iṣẹ rédíò aládánì tí nàìjíríà tí ń tàn káàkiri ní àwọn ìlú lọpọlọpọ jákèjádò orílẹ̀-èdè pẹlú lórí igbóhúnṣáfẹfẹ 1005 fm láti abuja àti ẹ̀kọ́ ìtàn ní àtẹ̀lẹ ifásílẹ̀ tí ìkéde lórí ọjọ kẹrin lè lógún oṣù kẹjọ ọdún 1992 daar communications plc tí ìpilẹ̀ṣẹ̀ nípasẹ̀ raymond dokpesi...
futa radio futa radio ile-ise agbohun safefe ti futa 931 mhz fm ni ile-ise redio ti federal university of technology akure ni akure ondo state nigeria o bere ise ni 19 november 2010citation needed ni odun 2015ile ise redio naa jona nipase ijamba ina mo-na-mo-na awon akekoo ti won kawe ni ale ni won gbiyanju lati dekun ...
inspiration fm community radio station in northampton united kingdom inspiration fm je rádíò ti ìlú ti o wa ni agbegbe northampton ni orile-ede united kingdom awón komuniti ni o n dari rádíò naa lati fi kó awón ará ilu lati fi da won lara ya ati lati fi ran awon ara ilu lowo si gbogbo northampton ni radio yii n de lati...
rhythm 937 fm port harcourt rhythm 937 fm jẹ́ rédíò ti iṣowo tí ó wà ní agbègbè old gra ti port harcourt ìpínlẹ̀ rivers ilé iṣẹ́ rédíò yìí á máa ṣe àwọn ìkéde òde òní wọ́n a máa gbé orin onírúurú síi bíi rb hip hop pẹ̀lú orin-ijó lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan àti reggae o jẹ ohun ini ati ẹ̀ka ìṣiṣẹ́ silverbird communications lábẹ́ ilé...
dessel locomotive factory
radio lagos brila fm
aso radio aso radio 935 fm jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé-iṣẹ́ rédíò ilẹ̀ nàìjíríà tó fìdí kalẹ̀ sí abuja ìjọpa àpapọ̀ ló sì ń darí rẹ̀ ìyẹn federal capital territory wọ́n dá ilé-iṣẹ́ rédíò yìí sílẹ̀ ní ọdún 1997 ẹni tó ṣagbátẹrù rẹ̀ ni rtd brigadier eneral jeremiah timbut useni tó fìgbà kan jẹ́ mínísítà abuja nígbà náà studi...
sobi fm sobi fm 1019 mhz jẹ́ ilé-iṣẹ́ rédíò kan tó wà ní ìlú ilorin ní ìpínlẹ̀ kwara ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n ṣèdásílẹ̀ rẹ̀ ní ọjọ́ kẹwàá oṣù keje ọdún 2017 ó sì wà ní orí-òkè sobi ní òpópónà shao olùdásílẹ̀ olùdásílẹ̀ sobi fm ni lukman akanbi olayiwola mustapha tó jẹ́ olóṣèlú ilẹ̀ nàìjíríà àti òṣìṣẹ́ báǹkì
nigeria custom broadcasting network nẹtiwọọki broadcasting customs nigeria ncbn jẹ́ apá mídíà tí ilé -iṣẹ́ kọ́sítọ́mù nàìjíríà tí a gbèrò láti ṣiṣẹ́ rédíò àti àwọn ibùdó ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán ní àwọn ìlú pàtàkì káàkiri gbogbo orílẹ̀ èdè lọwọlọwọ ó tàn káàkiri lórí rédíò 1067 mhz fm àti ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán ní abuja ní ọdún ...
melissa barrera melissa barrera martínez tí a bí ní ọjọ́ kẹrin osù keje ọdún 1990 jẹ́ òṣèrébìnrin àti akọrin ọmọ èdè èdè mexico ní orílẹ̀ èdè mexico wọ́n mọ́ fún ipa rẹ̀ nínú àwọn eré bi siempre tuya acapulco 2013 tanto amor 2015 àti club de cuervos 2017 káàkiri àgbáyé wọ́n mọ́ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi samantha carpenter ...
jasmin savoy brown jasmin savoy brown jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orilẹ-èdè amẹ́ríkà ó ṣeré nínú fíìmù hbo tí àpèlé rẹ̀ jẹ́ the leftovers 20152017 eré abc tí àpèlé rẹ̀ jẹ́ for the people 20182019 àti eré showtime tí àpèlé rẹ̀ jẹ́ yellowjackets 2021present ó tún ṣeré nínú àwọn fíìmù bi sound of violence 2021 scream 2022 àti scr...
akure ofosu forest reserve ibi ipamọ igbo akure ofosu wa ni guusu ìwọ oòrùn ni orile ede nàìjíríà o si bo ẹ̀rin lé ní ẹ̀wá dín-ní-irinwó onigun mẹrin kilomita akure ofosu ṣe pataki pupọ fun itoju awọn olugbe elegbede ni nàìjíríà iwadi ti a ṣe lakoko ọdun 2007 ri awọn itẹ ẹtalelọgbọn ni awọn ipo mẹrin laisi iran taara i...
àwòrán àwòrán jẹ́ ìfirọ́pò ohun tí a lè f'ojú rí ó lé wá ní ọ̀nà méjì tàbí mẹ́ta tàbí kí á wò ó nínú ohun tí a fi ń wo àwòrán tí ó fi lè fún wa ní ìtumọ̀ àwòrán náà gan an àwòrán lè jẹmọ́ ohun ìṣẹ̀mbáyé tí a yá kalẹ̀ pẹ̀lú kò di dandan kí àwòrán ó fi gbogbo ara hànde kàá tó mọ̀ wípé àwòrán ni àpẹẹrẹ irúfẹ́ àwòrán bẹ́ẹ̀...
devyn nekoda devyn nekoda tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kejìlá ọdún 2000 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè canada ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré láti ìgbà èwe rẹ̀ ó sì tún ṣeré nínú fíìmù scream vi tí wọ́n ṣàgbéjáde ní ọdún 2023 ìpìlẹ̀ rẹ̀ wọ́n tọ́ nekoda dàgbà ní ìlú brantford ontario ibẹ̀ náà ni wọ́n ó ti lọ ilé ìwé ó jẹ́ ọ...
kámẹ́rà kamẹ́rà jẹ́ àpótí rébété tí ó ní ojú tí a lè fi yan àwòrán yálà àwòrán onígun méjì tàbí mẹ́ta gbogbo àwọn kámẹ́rà ni wọ́n ma ń jẹ́ àpótí rébété kan tí a kàn pa tí ó ní ihò bíntín tí oyè ìmọ́lẹ̀ lè gbà kọjá láti gba àwòrán sílẹ̀ sínú díígí tí wọ́n ti ṣepa sínú rẹ̀ kámẹ́rà ní àwọn irinṣẹ́ kan tí wọ́n ma ń lò láti...
imí ọjọ́ chemical element with atomic number 16 imí ọjọ́ tabí sulfur sulphur ní èdè brítènì ni ó jẹ́ kẹ́míkà tí a ma ń ṣe àdámọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú àmì s tí númbà rẹ̀ jẹ́ 16 imí ọjọ́ jẹ́ ìkan nínú àwọn kẹ́míkà tí tí ó pọ̀ jùlọ ní orílẹ̀ àgbáyé àpapọ̀ imí ọjọ́ ati átọ́mù ni ó lábẹ́ oru tí kò lágbára ni ó ma ń yíra padà sí cyclic...
jenna ortega jenna marie ortega tí a bí ní ọjọ́ ọjọ́ kẹtàdínlọ́gún oṣù kẹsàn-án ọdún 2002 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ó bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣeré nínú àwọn fíìmù láti ìgbà èwe rẹ̀ ó sì gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ nínú eré jane the virgin 20142019 ó gbajúmọ̀ si lọ́pọ̀lọpọ̀ nígbà tí ó ṣe harley diaz nínú eré disney kan stuck...
ajílẹ̀ ajílẹ̀ ni a lè pè ní èròjà tí a ṣe yálà nílàna ìgbàlódé ni tàbí ti àbáléyé tí a wá dá tabí pòó mọ́ ilẹ̀ láti lè jẹ́ kí ilẹ̀ ó ní agbára láti mú ohun ọ̀gbìn jáde dára dára ju t'àtẹ̀yìnwá lọ a lè ṣe ajílẹ̀ pẹ̀lú àwọn ohun èlò nílé iṣẹ́ ìgbàlódé tàbí kí á ṣe é pẹ̀lú àwọn ohun èlò ìbílẹ̀ nípa iṣẹ́ ọ̀gbìn ìgbàlódé wọ...
arewa 24 arewa24 jẹ́ ìkánni tẹlifisiọnu satẹlaiti nàìjíríà tí o wà lóri dstv gotv àti startimes tí o ṣé àfihàn ìgbésí ayé tí agbegbe ariwa nigeria o jẹ́ ìkánni ọ̀fẹ́ sí afẹ́fẹ́ àkọ́kọ́ láti lo ede hausa
nigerian television authority aláṣẹ telifísọ̀nù ti nàìjíríà tàbí nta jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìgbóhùnsáféfé ti ìjọba tí ó jẹ́ ti ìjọba nàìj́iríà àti apákan ti ìṣòwò lá àkọ́kọ́ tí a mọ̀ sí ni nigerian television ntv ó ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ ní ọdún 1977 pẹ̀lú àṣẹ kan lórí ìgbóhùnsáféfé tẹlifísiọnu orílẹ̀-èdè lẹ́hìn gbígbà àwọn ilé-iṣẹ́ tẹ...
ogun state television tẹlifíṣọ̀n ìpínlẹ̀ ògùnogun state television tí a tún mọ̀ sí ogtv jẹ́ ilé-iṣẹ́ tẹlifíṣọ̀n ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó jẹ́ ti ìjọba ìpínlẹ̀ ògùn ó jẹ́ dídásílẹ̀ ní oṣù kejìlá ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n ọdún 1981 gẹ́gẹ́ bí i ilé-iṣẹ́ gbogboogbò comrade tunde oladunjoye ni ó jẹ́ alága ìgbìmò ilé-iṣẹ́ tẹlifí...
emmanuel tv emmanuel tv jẹ́ nẹ́tíwọkì tẹlifísàn onígbàgbọ́ pẹ̀lú olú ile ní ìpínlẹ̀ èkó nàìjíríà t b joshua ni olùdásílẹ̀ rẹ̀ òun ni olùṣọ́-àgùntàn àgbà àtijọ́ ti synagogue church of all nations scoan ní ìpínlẹ̀ èkó nàìjíríà ó' tún jẹ́ ọ̀kan lára ẹ̀rọ ayélujára iṣẹ́-ìránṣẹ́ kìrìtẹ́nì tí ó ṣe alábàápín jùlọ lóri youtube...
african magic african magic jẹ́ fọ́omù ìdàgbàsókè àti iṣẹ́ idán láàárín àṣà àti àwùjọ tí áfíríkà àti àwọn àjèjì ìtumò ọ̀rọ̀ idán ọ̀rọ̀ idán lè rọrùn ní òye bíi ìtọ́kasí ìṣàkóso tí àwọn ipá ti iṣẹ ṣiṣe kò wúwo ní ìhùwàsí ó sí jẹ́ iṣẹ ṣiṣe didoju lati ibẹrẹ iṣe idan sùgbón nipasẹ ifẹ ti alalupayida ni ero lati di ati lat...
arise news awọn iroyin arise jẹ́ ìkánni ìròyìn àgbáyé tí ó dá lórí ìlú lọ́ńdọ̀nù ó ní àwọn ilé -ìṣèré ní ilu new york london johannesburg abuja àti eko ìkánni náà ṣe àfihàn àkóónú áfíríkà amerika àti yuroopu arise broadcasting ltd ni ó ń ṣiṣẹ́ rẹ̀ èyítí ó jẹ́ ohun ìní nípasẹ̀ onímọ̀ràn oníròyìn nàìjíríà nduka obaigbena...
akbc akwa ibom state broadcasting corporation kikuru akbc uhf channel 45 jẹ́ ilé-iṣẹ́ tẹlifísíọ̀nù ti ìjọba ní uyo akwa ibom akwa ibom broadcasting corporation jẹ́ dídá sílẹ̀ ní ọjọ́ 4 oṣù kẹrin ọdún 1988 àti pé ó jẹ́ àkọ́kọ́ àti ìbùdó tẹlifíṣíọ̀nù agbègbè nìkan akbc pese tẹlifísíọ̀nù méjèèjì àti àwọn iṣẹ́ rédíò ó ń da...
silverbird group silverbird group jẹ́ ilé-iṣẹ́ mídíà pẹ̀lú àwọn ẹ̀ka ní rédíò tẹlifíṣọ̀nù ilẹ̀ títà àti àwọn sinimá tí ó jẹ́ olú ilé-iṣẹ́ ní èkó orílẹ̀-èdè nàìjíríà ilé-iṣẹ́ náà jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọdún 1980 nípasẹ̀ ben murray-bruce àti pé ó ka àwọn sinimá silverbird àti mbgn àti láàárín awọn ohun-ìní rẹ̀ àwọn ìpín ìṣòwò ...
africa independent television africa independent television tí a tún mọ̀ nípa àdàpè rẹ̀ ait jẹ́ olùgbúhùnsáfẹ́fẹ́ tẹlifísàn ti aládàáni ní nigeria ó ń ṣiṣẹ́ láì sanwó gbọ ní nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí aládàákọ́ tó tóbi jù lọ nẹ́tíwọ́kì tẹlifíṣan orí ilẹ̀ tí ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ilé iṣẹ́ ní mẹ́rìnlélógún nínú àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìnd...
samara weaving samara weaving tí a bí ní ọjọ́ kẹtalélógún oṣù kejì ọdún 1992 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè austrilia ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré rẹ̀ nípa kíkó ipa kirsten mulroney nínú out of the blue 2008 ó gbajúmọ̀ nígbà tí ó kó ipa indi walker nínú eré home and away 20092013 èyí tí ó gba àmì-ẹ̀yẹ australian academy of cinema...
the guardian nigeria the guardian jẹ́ ìwé-ìròyìn ojoojúmọ́ olómìnira ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 1983èyí tí ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn guardian tó wà ní ìpínlè eko ní nàìjíríà ìtàn ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn the guardian jẹ́ dídá sílẹ̀ ní ọdún 1983 láti ọwọ́ alex ibru ẹni tí ó jẹ́ oníṣòwò àti stanley macebuh tó j...
complete sports complete sports jẹ́ ìwé-ìròyìn eré-ìdárayá orílẹ̀-èdè nàìjíríà lójoojúmọ́ ó sì ní orílé-iṣẹ́ rẹ̀ ní isolo ìjọba ìbílẹ̀ kan ní ìpínlẹ̀ èkó ọdún 1995 ni wọ́n kọ́kọ́ tẹ̀ ẹ́ jáde gẹ́gẹ́ bí ìwé-ìròyìn ti complete communications limited àti pé ó ti di ọ̀kan lára àwọn ìwé-ìròyìn tó pọ̀ jù lọ ní naijiria ìwé-ìr...
ẹgbẹ silverbird
awọn iroyin dide
hayden panettiere hayden lesley panettiere tí a bí ní ọjọ́ kanlelogun oṣù kẹjọ ọdún 1989 jẹ́ òṣèrébìnrin àti akọrin ọmọ orílẹ̀ èdè amerika ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ́ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi claire bennet nínú eré heroes 20062010 àti gẹ́gẹ́ bi juliette barnes nínú eré nashville 20122018 ó gba àmì ẹ̀yẹ méjì fún golden globe award for ...
online tiketi online tiketi alaye tikẹti ori ayelujara ni ọna ti o rọrun ati mimọ fojuinu pe o fẹ gba ibikan ni lilo ọkọ oju-irin ilu bii ọkọ akero tabi ọkọ oju-irin alaja nigbagbogbo lati gba tikẹti o ni lati lọ si ọfiisi tikẹti tabi ibudo gbigba agbara nibiti o ti laini ati duro de akoko rẹ eyi le gba akoko paapaa la...
niche theniche jẹ́ ìwé-ìròyìn orí ayélujára ójóójúmọ̀ tí orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ìṣètò ní 20 oṣù kẹrin ọdún 2014 ní ikeja ìpínlẹ̀ èkó theniche tí forúkọsílẹ lábẹ́ àwọn ilé-iṣẹ àti òfin àwọn ọrọ tì 1990 àti pé ó jẹ atẹjáde nípasẹ̀ acclaim communications limited ìtàn theniche jẹ ìwé ìròyìn orí ayélujára tí ó dá nípasẹ̀ àw...
media trust media trust jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn aládàáni tó wà ní abuja tó máa ń tẹ ìwé-ìròyìn daily trust weekly trust sunday trust ní èdè gẹ̀ẹ́sì àti ìwé-ìròyìn aminiya ní èdè hausa bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n máa ń ṣàgbéjáde ìròyì ilẹ̀ africa tí wọ́n ń pè ní kilimanjaro ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn aṣáájú ilé-iṣẹ́ ìgbéròyìn jáde ní ...
naija news nigerian online newspapernaija news jẹ́ ile-ise oni ìwé ìròyìn ẹ̀rọ ayélujára tí nàìjíríà wọ́n dáa sílè ni ọdún 2016 nípa ọgbeni opemipo olawale adeniyi history wọ́n dá naija news sílẹ̀ ní ọdún 2016 pẹ̀lú ati leyin polance media limited ní ọdún 2021 ile-ise yìí kó lọ sí ikoyi ni ìpínlè eko láti tẹsiwaju nínú...
elizabeth olsen elizabeth chase olsen tí a bí ní ọjọ́ kẹríndínlógún oṣù kejì ọdún 1989 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà wọ́n bi ní sherman oaks california olsen ti bẹ̀rẹ̀ ṣíṣe láti ìgbà tí ó ti jẹ́ ọmọ ọdún merin ó kópa nínú fíìmù fún ìgbà àkọ́kọ́ nínú fíìmù martha marcy may marlene ní ọdún 2011 ó sì gba àmì-ẹ̀y...
ìjàpá lọ jẹ àsè ní ilé àdán ìfáàrà ní ìgbà láéláé tí àwọn àròsọ fi yé wa wípé àwọn ẹranko a máa sọ̀rọ̀ bí ènìyàn ìjàpá jẹ́ ẹranko tí ó kún fún ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ púpọ̀ púpọ̀ ní akoko yi itan sọ fun wa wipe ọrẹ timotimo ni ijapa ati àdán ijapa n gbe ilẹ nigbati adan n gbe ori igi kan lẹba ọsa ṣugbon iṣẹlẹ kan ṣẹ ni akoko yii ...
evangeline lilly nicole evangeline lilly tí a bí ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹjọ ọdún 1979 jẹ́ òṣèrébìnrin àti òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀ èdè kanada ó gbajúmọ̀ nígbà tí ó kó ipa kate austen nínú eré tí àpèlé rẹ̀ jẹ́ lost 20042010 òun sì ló jẹ́ kí wọ́n yán fún àmì-ẹ̀yẹ golden globe award for best actress in a drama series lilly ti kópa n...
kánádà kánádà
tessa thompson tessa lynne thompson tí a bí ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹsàn-án ọdún 1983 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè amerika ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré pẹ̀lú ilé isé los angeles women's shakespeare nígbà tí ó ń kàwé ní ilé ìwé santa monica college ó wà nínú eré the tempest àti romeo and juliet ipa rẹ̀ nínú eré romeo a...
union bank of nigeria union bank of nigeria plc jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé-ìfowópamọ́ ilẹ̀ nàìjíríà tí olú-ilé-iṣé rẹ̀ wà ní victoria island lagos ó ti ń ṣiṣẹ́ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà láti ọdún 1917 àkópọ̀ union bank jẹ́ ilé-ìfowópamọ́ ńlá tó ń ṣiṣẹ́ fún àwọn ènìyàn ilé-iṣẹ́ kékeré àti alábọ́dé pẹ̀lú àwon ilé-iṣẹ́ ńlá ní o...
florence kasumba florence kasumba tí a bí ní ọjọ́ kẹrindínlógbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1976 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè uganda àti jamini ọ̀pọ̀ mọ́ fún ipa tí ó kó gẹ́gẹ́ bí enikan tí ó ń jẹ́ ayọ̀ nínú fíìmù àwọn fíìmù ilé isé marvel cinematic universe bi ' 2016 black panther 2018 ' 2018 àti 2022 ó tún kó ipa ayò nínú fíì...
fidelity bank nigeria fidelity bank tí a tún mọ̀ sí fidelity bank plc jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé-ìfowópamọ́ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí olú ilé-iṣé wọn wà ní victoria island lagos ó jẹ́ ilé-ìfowópamọ́ tó ti gbàwé àṣẹ tí central bank of nigeria sì ti fòǹtẹ̀ lù gẹ́gẹ́ b́i báǹkì oníṣòwò ilé-ìfowópamọ́ ti fidelity ti pẹ̀ka láti...
polaris bank limited polaris bank limited jẹ́ ọ̀kan lára àwon ilé-ìfowópamọ́ ilẹ̀ nàìjíríà ó gba ìwé-àṣẹ lọ́wọ́ central bank of nigeria èyí tó jẹ́ olùṣàkóso àwọn ilé-ìfowópamọ́ ní orílẹ̀-èdè náà ní oṣù kẹwàá ọdún 2022 strategic capital investment limited scil gba báǹkì yìí láti sọ ọ́ di ohun ìní wọn àwòpọ̀ polaris bank...
adetunji femi fadina adetunji femi fadina ni alága ẹgbẹ́ tourism practitioners of nigeria atpn èyí tó wà ní apá ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ nàìjíríà òun sì ni adarí àgbà ti ilé-iṣẹ́ jethro tours and awori initiative ó sì tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ trade promotion board fún ẹ̀ka tó ń rí sí ètò ìṣòwò àti ilé-iṣẹ́ ní ìpínlẹ̀ èkó ètò ẹ̀kọ́ ilé...
ajégúnlẹ̀ ajégúnlẹ̀ tí eọ́n tún ń dàpè ní aj city or simply aj jẹ́ agbègbè kan ní ìpínlẹ̀ èkó tí ó wà ní abẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ ajérọ̀mí ifẹ́lódùn ajégúnlẹ̀ pààlà pẹ̀lú ibùdó etíkun àpápá wharf àti tincan tí wọ́n jẹ́ ibùdó ìkẹ́rù wọlé lórí omi tí ó tòní jùlọ ní ìpínlẹ̀ èkó tí oríṣiríṣi nkan ti wọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà iye awọ...
ẹ̀yà awori awori jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà àwọn ọmọ yorùbá tí ń sọ èdè kan pàtó èyí tí í ṣe èdè yorùbá ìwọ̀n agbègbè ní ìbámu pẹ̀lú àṣà àwọn ẹ̀yà àwórì wà ní ìpínlẹ̀ ògùn àti ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà àwọn ìlú bíi ikorodu epe badagry ota ado-odo isheri igbesa agbara ilobi àti tigbo jẹ́ ibùgbé àwọn awori láàárín...
koko komégne koko komégné jẹ ayaworan ti o kale si ilu douala ati olupolowo ti aaye aworan asiko ni ilu kamẹrika igbesi aye ati iṣẹ abi koko komégné ni odun 1950 ni batoufam ni ọdun 1956 o lọ si yaoundé nibiti o ti lọ si ile-iwe ati pe o bẹrẹ iyaworan ati gbigbọ gbogbo awọn orin ni 1960-62 o ṣe agbejade ere akọkọ rẹ le...
dotun popoola dotun popoola a bi ni ọdun 1981 ni ilu eko jẹ olorin ọmọ orilẹede naijiria ti ode oni ti o ṣe amọja ni fifin irin amuṣiṣẹpọ o ṣẹda awọn ege iṣẹ ọna lati awọn irin alokuirin ti a sọnù awọn iṣẹ rẹ ni idojukọ lori yiyi idọti pada si awọn iṣura idoti si awọn iyùn ati egbin si ọrọ nipa sisọ awọn egbin ti o hal...
yetunde ayeni-babaeko yetunde ayeni-babaeko ojoibi 1978 je oluyaworan omo naijiria igbesi aye yetunde ayeni-babaeko ni a bi ni enugu agbègbè apáìlàoòrùn nàìjíríà ni ọdun 1978 bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ nàìjíríà ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ará jámánì o gbe lọ si jamani bi ọmọde lọ si ile-iwe giga nibẹ o si pari iṣẹ ikẹkọ fọto yiya ni studio b...
trade union congress àjọ àwọn òṣìṣẹ́ àgbà trade union congress of nigeria tuc jẹ́ ọ̀kan lára àjọ national trade union federation lórílẹ̀-nigeria tí ó dálé ṣíṣojú àwọn òṣìṣẹ́ àgbà
national trade union federation national trade union federation jẹ́ àgbájọpọ̀ àwọn àjọ ayédáadé àti àjà fẹ́tọ̀ọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ní orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan ó fẹ́ẹ̀ jẹ́ pé gbogbo orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan ni ó ní ajọ̀ yìí káàkiri ní orílẹ̀-èdè wọn tí wọ́n sì ní ilé-iṣẹ́ àjọ yìí káàkiri àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn ni ju ilé-isé kan lọ fún ...
george edozie george edozie ojoibi 1972 je oluyaworan omo naijiria ngbe ni lagos nigeria igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ won bi george edozie ni 11 oṣu karun ọdun 1972 o lọ si ile-iwe alakọbẹrẹ university ni nsukka ile-iwe iranti iranti washington onitsha edozie kawe fine applied arts ni yunifasiti ti benin ni ilu benin nibi ...
dele jegede dele jegede ti a ṣe ni aṣa bi dele jegede jẹ oluyaworan ara ilu naijiria-amẹrika akoitan aworan alaworan alabojuto alariwisi aworan alabojuto iṣẹ ọna ati olukọ jegede jẹ olukọni post-doctoral agba ni ile-ẹkọ smithsonian ni washington dc 1995 o kọ ni awan of ile iwe ni spelman college atlanta bi alejo fulbri...
folashodun adebisi shonubi folashodun adebisi shonubi tí wọ́n bí lọ́jọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1962 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nigeria àti gómìnà-fìdíhẹ ilé-ìfowópamọ́-àgbà the central bank of nigeria tí ààrẹ bọlá ahmed tinubu yàn lọ́jọ́ kẹwàá oṣù kẹfà ọdún 2023 láti rọ́pò gómìnà-àná ilé-ìfowópamọ́-àgbà godwin emefiele tí wọn dá d...
eewo ninu awon igbagbo yoruba èwọ̀ ní ilẹ̀ yorùbá èwọ̀ jẹ́ ohun tí àwọn ènìyan àwùjọ kan gbà gẹ́gẹ́ bí ìwà ìdọ̀tí ìwà ìtìjú ìwà ẹ̀gbin tí a kò gbọdọ̀ ṣe láarín àwùjọ lára rẹ̀ ni jijoko sori odó awọn eniyan maa n lo odó lati pese diẹ ninu awọn ounjẹ ti wọn fẹ julọ gẹgẹbi iyán fufu ati bẹbẹ lọ ikilọ pataki kan lẹhinna fu...
àtòjọ àwọn gómìnà ìpínlẹ̀ èkó èyí ni àtòjọ àwọn gómìnà àti adarí ológun tí ó ti dárí ìpínlè ẹ̀kọ́ láti ìgbà tí wọ́n ti da kalẹ̀ ní ọjọ́ mẹ́tàdínlógbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 1967
bernice oasis outreach bernice oasis outreach je iṣẹ iranti ti o mọ ipa lati siṣẹ fun alaini ati lati yipada awọn ọgbọn awọn aye siwaju ninu awọn ilu ti o gbajumo ifihan wa ni lati gba ifẹ ipilẹ ati awọn ohun ti o nilo fun awọn ti o wọ ifiṣọra laaye ni odo lẹhinna ni awọn ipa rẹ ati awọn ọdọ wa si awọn wa ni opin awa n...
bernice akinwande bernice akinwande ni olugbeji alagbeka ti o dara julọ ti o dun lati gba ifẹ ni ifiṣẹyan rẹ ni ifiṣẹyan rẹ ti o dara julọ ati lati ifiṣẹyan o ti da lori aye ni odo ti o mu ifẹjọmọluwabi awọn ọmọde rẹ si ona ifẹ pataki ti o dara julọ ifẹjọmọluwabi bernice ati lati ṣe ifẹjọmọluwabi ati lati ro ṣe afẹfẹ n...
african leadership university african leadership university alu jẹ iṣẹ iranti to da lori igbala awọn alaboyun ti o wulo ni afrika nipa irinṣẹ ti o ni lati pese iṣẹdọmu ti o dara julọ alu fi awọn olori iṣẹrọ ifunni ati ojogbon lori iṣẹ ti o nilo fun wọn lati fi gba iṣẹsi aye ti o wulo ni afrika si awọn alaboyun iṣẹdọmu ...
christopher gwabin musa ọ̀gágun major general christopher gwabin musa tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1967 jẹ́ ọ̀gágun-àgbà tí ó ga jùlọ fún ààbò orílẹ̀-èdè nigeria ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ kàdúná sùgbọ́n tí wọ́n bí sí sokoto ààrẹ bọlá ahmed tinubu ni ó yàn án gẹ́gẹ́ bí ọ̀gágun-àgbà tí ó ga jùlọ fún ààbò orílẹ...
kayode egbetokun kayode egbetokun tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrin oṣù kẹsàn-án ọdún 1964 jẹ́ ọ̀gá-àgbà ọ̀lọ́pàá yànyàn ọmọ ìpínlẹ̀ ògùn lórílẹ̀-èdè nigeria ààrẹ bọlá ahmed tinubu ni ó yàn án lọ́jọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹfà ọdún 2023 láti rọ́pò ọ̀gá-àgbà ọ̀lọ́pàá yàn yàn-àná usman alkali baba lẹ́yìn tí ó kéde yíyọ ọ́ kúrò nípò lọ...
taoreed lagbaja 23rd chief of army staff nigeria ọ̀gágun major general taoreed abíọ́dún lágbájá ni wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 1968 jẹ́ ọ̀gágun-àgbà tí ó gboyè major general nínú iṣẹ́ ológun orílẹ̀ - èdè nigeria òun ni ọ̀gágun-àgbà yányán àwọn ológun nigeria chief of army staff he was appointed on 19 j...
alex oti alex otti jẹ̀ gómìnà ìpínlẹ̀ abia o dii gómìnà ní ìdìbò gbogbogbò nii ọdún 2023 ní abẹ ẹgbẹ labour
agbu kefas jẹ́ olóṣèlú nàìjíríà àti olóṣèlú nàìjíríà tó ti fẹ̀yìn tì lẹ́nu iṣẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ taraba láti ọdún 2023
abba kabir yusuf a bi abba kabir yusuf ni ojo karun osu kinni odun 1963 o je oloselu naijiria to je gomina ipinle kano ni odun 2023 o sise gege bi komisanna ti igbimo alase ni ipinle kano lati odun 2011 si 2015
dauda lawal ojoibi 2 osu kesan odun 1965 je okunrin banki ati oloselu omo naijiria ti o je gomina ipinle zamfara wọ́n dìbò yàn án lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú peoples democratic party pdp nínú ìdìbò gómìnà orílẹ̀-èdè nàìjíríà lọ́dún 2023 tí wọ́n ṣẹ́gun gomina bello matawalle ti ẹgbẹ́ òṣèlú apc
alifabeeti oduduwa alifabeeti odùduwà ni won da lati ko èdè yorùbá ni odun 2017 o ti wa ni igbega ni mejeji nàìjíríà ati benin awọn lẹta ti alifabeeti awọn nọmba
alifabeeti
alfabeti
isaiah oghenevwegba ogedegbe isaiah oghenevwegba ogedegbe ojoibi 14 osu kefa 1991 je omo orile-ede naijiria ti o n se elesin ati oluso buloogi awon asotele ogedegbe jo nipa orile-ede naa awon asotele ogedegbe tun je nipa aare orile-ede naijiria tele ogedegbe ni buloogi kan ti won n pe ni warri times buloogi naa ni oged...
bako ni lati rii dapo ilesa to daura 1 ounjẹ ẹran ara ti awọn ohun ọsin wa ko ni itumọ bi tiwa wọn ko jẹun ko ni tito nkan lẹsẹsẹ tẹlẹ nipasẹ itọ ni ifun kukuru ati pe o le jiya lati isanraju ti wọn ba jẹ aijẹunnuwọnnu ti o ni idi ti o ṣe pataki lati mọ awọn aini gidi ti aja rẹ lati jẹ ki o ni ilera ọjọ ori aja puppy o...
darlington nwokocha darlington nwokocha jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó jẹ́ asójú agbègbè abia central federal láti ọdún 2023 kí ó tó di sénátọ̀ ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìgbìmò asofin kékeré tí ó sójú isiala-ngwa north/isiala-ngwa south láàrin 2015 sí 2019 nwokocha jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ abia state house of assembly láàrin ...
ishaku abbo ishaku elisha abbo tí a bí ní mubi north nàìjíríà jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà òun ni sénátọ̀ tí ó ń ṣe aṣojú àgbègbè adamawa north senatorial district ní ìpínlẹ̀ adamawa ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òsèlú all progressives congress apc lọ́wọ́ lọ́wọ́ ipa rẹ̀ nínú òsèlú ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kejì ọdún 2019 wọ́n y...
binos dauda yaroe sen binos dauda yaroe jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà àti sénátọ̀ tí ó ń sójú agbègbè adamawa south senatorial district ti ìpínlẹ̀ adamawa ní ilé ìgbìmò aṣòfin àgbà lọ́wọ́lọ́wọ́ ìpìlẹ̀ rẹ̀ wọ́n bí binos dauda yaroe ní ọjọ́ kínní oṣù kínní ọdún 1955 ní wagole abúlé kan ní agbègbè ribadu ward ti ìjọ...
gwagwalada gwagwalada jẹ́ ọ̀kan lára àwọn íjọba ìbílẹ̀ ní federal capital territory orílẹ̀ èdè nàìjíríà gwagwalada ní ilẹ̀ tí ó tó 1043 km2 àti olùgbé 157770 ní ìgbà ìkànìyàn ti ọdún 2006 kí wọ́n wọ́n tó dá gwagwalada kalẹ̀ ó wà lábẹ́ agbègbè kwali ti abuja tẹ́lẹ̀
abidi braille awọn abidi braille jẹ eto kikọ fun afọju ti a fi ọwọ ka awọn abidi braille wa fun ọpọlọpọ awọn ede pẹlu èdè yorùbá lẹta awọn lẹta ti alifabeeti