raw_text
stringlengths
2
128k
warri times warri times ni aaye ayelujara ti isaiah ogedegbe ni warri onkiwe nla amurika kan frederic will mu nuba warri times ninu iwe 2017 ro awon itokasi yi ni a kukuru article jọwọ mu yi
bola tinubu
threads thread jẹ́ ìkànnì ayélujára tí ó jẹ́ ìní ilé isé meta ó dà bi àwọn ìkànnì ayélujára bi twitter àwọn tí ó wà lórí ìkànnì náà le fi ọ̀rọ̀ àti fọ́tò léde wọ́n le fi èsì sí ọ̀rọ̀ ìkànnì náà wà lórí ios àti android àwọn tí ó ń lò ó dé iye mílíọ̀nù ọgọ́rin ní àárín wákàtí méjìdínládọ́tá wọ́n fi ìkànnì threads lélẹ̀ n...
mai mala buni mai mala buni tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kọkànlá ọdún 1967 jẹ́ olóṣèlú tí ó ti ṣe gómìnà eí ní ìpínlẹ̀ yobe ní ọdún 2019 ati ọm9 lrílẹ̀-èdè nàìjíríàòun noi wọ́n dìbò yàn nínú ìdìbò tó wáyé ní ọdún 2019 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú all progressives congress ṣáájú kí ó di gómìnà ni ó tinwà nípò akọ̀wé àgbà f...
umo eno umo bassey eno tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹrin ọdún 1964 jẹ́ olùṣọ́ àgùtàn ilé-ìjọsìn all christain ministary international àti olóṣèlú tí ó tún jẹ́ gómìnà ní ìpínlẹ̀ akwa ibom nínú ìdìbò tó wáyé ní ọdún 2023 ó sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni kọmíṣánà tẹ́lẹ̀ rí fún ọ̀rọ̀ ilẹ̀ àti omi àlùmọnì fún...
andrés iniesta andrés iniesta luján tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù karùn-ún ọdún 1984 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀ èdè spain ó wà lára àwọn tí ọ̀pọ̀ kà sí agbábọ́ọ̀lù àárín tí ó da jù ní àgbáyé iniesta lọ ọ̀pọ̀lopọ̀ ọdún rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi agbábọ́ọ̀lù ní barcelona ní ibi tí ó ti jẹ́ adarí ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù náà fún ṣáà mẹ́ta inie...
andrea pirlo andrea pirlo tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún 1979 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀ èdè italy tí ó jẹ́ olùtoni àgbà ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù serie b sampdoria ó wà lára àwọn tí ọ̀pọ̀lopọ̀ kà sí agbábọ́ọ̀lù ipò àárín tí ó da jùlọ pirlo bẹ̀rẹ̀ sí ń gba bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ brescia ní ọdún 1995 ó jáwé olúborí borí serie b ní ọd...
tom holland thomas stanley holland tí a bí ní ọjọ́ kínní oṣù kẹfà ọdún 1996 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè britain ara àwọn àmì ẹyẹ rẹ̀ ni british academy film award àti saturn awards mẹ́ta àwọn àtẹ̀jáde míràn ti pèé ní òṣèré tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní ìran rẹ̀ holland jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́sàn-án nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ erẹ́ ṣíṣe ó darapọ̀ ...
tom hiddleston thomas william hiddleston tí a bí ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kejì ọdun 1981 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè britain ó gbajúmọ̀ káàkiri orílẹ̀ èdè nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ń kópa gẹ́gẹ́ bi loki nínú àwọn eré marvel cinematic universe mcu ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú thor ní ọdún 2011 ó sì ti farahàn nínú àwọn eré mìíràn bi avengers tí ...
samuel l jackson samuel leroy jackson tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kejìlá ọdún 1948 jẹ́ òṣèré ọmọ orilẹ̀-èdè actor amerika ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèré tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní ìran rẹ̀ a àwọn fíìmù tí ó ti ṣeré ti pa iye owó tí ó lé ní bílíọ́nù mẹ́tàdínlógún dọ́là 27 billion èyí mú kí ó jẹ́ òṣèré kejì tí àwọn eré rẹ̀ ...
chess ayò chess jẹ́ ayò tí a ma ń ta lórí tábìlì lábẹ́lé láàrín ònta ènìyàn méjì ònta kọ̀ọ̀kan ni wọ́n ma dá ayo wọn mọ̀ pẹ̀lú kí ìkan apá ilé kan dúdú kí ìkejì sì funfun àwọn ònta wọ̀nyí ni wọn yóò ma darí àwọn ayò tí wọ́n jẹ́ ikọ̀ ọmọ ogun ilé kọ̀ọ̀kan tí wọ́n ń pè ní chess pieces gbogbo ète àti èrò ònta kọ̀ọ̀kan ni ...
josh brolin josh james brolin tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kejì ọdún 1968 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà josh jẹ́ ọmọ james brolin ó sì di gbajúmọ̀ nígbà tí ó ṣeré nínú fíìmù the goonies 1985 lẹ́yìn òpò ọdún brolin tún ṣeré nínú fíìmù no country for old men 2007 ó gba àmì-ẹ̀yẹ academy award for best supporting actor f...
letitia wright letitia michelle wright tí a bí ní ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹ̀wá ọdún 1993 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè guyana mọ́ britain ó bẹ̀rẹ̀ isẹ́ òṣèré pẹ̀lú àwọn fíìmù bi top boy coming up chasing shadows humans doctor who àti black mirror wọ́n yàn sí ara àwọn tí ó tó sí àmì-ẹ̀yẹ primetime emmy award ó di gbajúmọ̀ n...
youtube youtube jẹ pinpin fidio ori ayelujara ti amẹrika ati ipilẹ ẹrọ awujọ awujọ ti o wa ni san bruno california amẹrika wiwọle si agbaye ti ṣe ifilọlẹ ni kínní 14 2005 nipasẹ steve chen chad hurley ati jawed karim o jẹ ohun ini nipasẹ google ati pe o jẹ oju opo wẹẹbu keji ti a ṣabẹwo julọ lẹhin wiwa google youtube n...
simu liu simu liu tí a bí ní ọjọ́ kandínlógún oṣù kerin ọdún 1989 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè kanada ó gbajúmọ̀ fún kíkọ́ ipa shang-chi nínú fíìmù marvel cinematic universe shang-chi and the legend of the ten rings tí ó jáde ní ọdún 2021 ó tún kó ipa gẹ́gẹ́ bi jung kim nínú fíìmù cbc television kim's convenience ó sì gba ...
ben affleck benjamin géza affleck tí a bí ní ọjọ́ keedógún oṣù kẹjọ ọdún 1972 jẹ́ òṣèré àti aṣe fíìmù ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ó tì gba àmì-ẹ̀yẹ academy awards fún àwọn fíìmù rẹ̀ affleck bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣeré láti ìgbà èwe nígbà tí ó ṣeré nínú eré pbs tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ the voyage of the mimi 1984 1988 ó tún padà ṣeré nínú daz...
àgbègbè ìjọba ìbílẹ̀ abadam abadam jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìjọba ìbílẹ̀ ìjọba ìbílẹ̀ ìpínlẹ̀ borno nàìjíríà ní apá ìwọ oòrùn lake chad àwọn àlà rẹ̀ ni chad àti niger ó sì sún mọ́ cameroon ní ọdún 2016 àwọn olùgbé rẹ̀ tó 140000 olú ìlú rẹ̀ wà ní malumfatori ètò àbò àti ìlera ara wà lára àwọn ìdojúkọ ní agbẹ̀gbẹ̀ ìjọba ìbílẹ...
àgbègbè ìjọba ìbílẹ̀
jared leto jared joseph leto tí a bí ní ọjọ́ kẹrindínlógbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1971 jẹ́ òṣèré àti olórin ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ nínú iṣẹ́ òṣèré tí ó ti ń ṣe fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún àwọn àmì ẹyẹ bi academy award àti golden globe award pẹ̀lú pẹ̀lú ó gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ orin kíkó gẹ́gẹ́ bi ara àwọn ọ...
terence stamp terence henry stamp tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù keje ọdún jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè britain ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi alátakò nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré ó gba àmì-ẹ̀yẹ golden globe award cannes film festival àti silver bear wọ́n sì yán kún ara àwọn tí ó tó fún àmì-ẹ̀yẹ academy award àti bafta awards mé...
brandon routh brandon james routh tí a bí ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹ̀wá ọdún 1979 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ó ṣeré superman nínú fíìmù 2006 film superman returns èyí tí ó mú kí ó gbajúmọ̀ káàkiri orílẹ̀ èdè ní ọdún 2011 ó ṣeré nínú fíìmù ó tún kó ipa daniel shaw nínú fíìmù nbc tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ chuck ara àwọn eré m...
antje traue antje traue tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kínní ọdún 1981 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè jámánì ó ṣeré nínú fíìmù gẹ̀ẹ́sì fún ìgbà àkọ́kọ́ nígbà tí ó ṣeré nínú pandorum ó di gbajúgbajà káàkiri àgbáyé nígbà tí ó ṣeré nínú gẹ́gẹ́ bi faora nínú fíìmù man of steel 2013 àti the flash 2023 àti gẹ́gẹ́ bi agnes nielse...
billy crudup william gaither crudup tí a bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù keje ọdún 1968 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orilẹ-èdè amẹ́ríkà ipá rẹ̀ nínú fíìmù jesus' son 1999 jẹ́ kí wón yàn mọ́ àwọn tí ó tó sí independent spirit award for best male lead ó tún ṣeré nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré bi almost famous 2000 big fish 2003 ' 2006 watchmen 2009 pub...
adewale akinnuoye-agbaje adewale akinnuoye-agbaje tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1967 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi simon adebisi nínú eré oz mr eko nínú lost lock-nah nínú the mummy returns nykwana wombosi nínú the bourne identity heavy duty nínú ' kurse nínú ' ki...
laurence fishburne laurence john fishburne iii tí a bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù keje ọdún 1961 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ emmy award ní ẹ̀mẹ́ta tí àti àmì ẹyẹ tony award ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi morpheus nínú the matrix series 19992003 jason furious styles nínú eré john singletontí àkòrí rẹ̀ ...
joel olaniyi oyatoye ọmọ ọba joel ọláníyì ọyátóyè tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí bàbá àṣà jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti kánádà ó jẹ́ akọ ewì olùgbóhùnsafẹ́fẹ́ oníṣẹ́ ara-ẹni ajíyìnrere olùpolongo àti olùgbélárúgẹ àṣà àti ìṣe yorùbá ibẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí ọláníyì ní ìpínlẹ̀ kwara ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ni 27 january 19...
joel olaniyi owatoye
joel olaniyi ọyátóyè
peter sarsgaard john peter sarsgaard tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1971 jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ó ṣeré fún ìgbà àkọ́kọ́ nínú eré dead man walking ní ọdún 1995 ó tún ṣeré nínú fíìmù independent tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ another day in paradise àti nínú desert blue ní ọdún kan náà sarsgaard kópa raoul nínú eré t...
jeffrey dean morgan jeffrey dean morgan tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹrin ọdún 1966 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi negan nínú fíìmù amc horror drama tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ the walking dead 20162022 àti nínú 2023-present ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ oríyìn fún ipa rẹ̀ nínú eré yìí àwọn er...
hilarie burton hilarie ros burton tí a bí ní ọjọ́ kínní oṣù keje ọdún 1982 tí àwọn mìíràn mọ̀ sí hilarie burton morgan jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ó ti fi ìgbàkan jẹ́ olótùú fún ètò mtv tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ total request live ó ṣeré gẹ́gẹ́ bi peyton sawyer nínú eré wb àti cw tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ one tree hill 20032009 l...
amy adams amy lou adams tí a bí ní ọjọ́ ogún oṣù kẹjọ ọdún 1974 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ó gbajúmọ̀ fún apepe àti àwàdà nínú àwọn eré tí ó ma ń ṣe ó wà lára àwọn òṣèrébìnrin tí wọ́n ń san owó fún jùlọ ní àgbáyé ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ àmì-ẹ̀yẹ bi golden globe awards méjì wọ́n sì yán ní emefà mọ́ ara àwọn ...
cillian murphy cillian murphy tí a bí ní ọjọ́ kàrúnlélógún oṣù kàrún ọdún 1976 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè ireland ó ṣeré fún ìgbà àkọ́kọ́ nínú eré enda walsh ltí àkòrí rẹ̀ jẹ́ disco pigs ní ọdún 1996 àwọn eré míràn tí ó ti farahàn ni 28 days later 2002 nínú intermission 2003 red eye 2005 the wind that shakes the barley 2...
aaron eckhart aaron edward eckhart tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kẹta ọdún 1968 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà wọ́n bi ní cupertino california eckhart lọ sí orílẹ̀ èdè united kingdom nígbà tí ó wà ní èwe ó bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣeré nígbà tí ó sì wà ní ilé ìwé kí ó tó lọ sí australia ó fi ilé-ìwé high school kalẹ̀ láì gba ìwé ẹr...
guosa guosa jẹ́ ìfọ̀rọ̀wérọ̀ tí a kọ́ ní ìpilẹ̀ṣẹ̀ látọwọ́ alex igbineweka ní 1965 a ṣe é láti jẹ́ àkópọ̀ àwọn èdè ìbílẹ̀ nàìjíríà àti láti sìn gẹ́gẹ́ bí èdè kan sí ìwọ̀ oòrùn áfíríkà
morena baccarin morena silva de vaz setta baccarin tí a bí ní ọjọ́ kejì oṣù kẹfà ọdún 1979 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi inara serra nínú eré firefly àti serenity gẹ́gẹ́ bi vanessa nínú eré deadpool jessica brody nínú eré showtime tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ homeland dr leslie lee thompkins n...
malin akerman malin maria åkerman tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù karùn-ún ọdún 1978 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè sweden ní àárín ọdún 2003 sí 2004 ó farahàn nínú eré the utopian society 2003 àti harold kumar go to white castle 2004 lẹ́yìn ìgbà tí ó farahàn nínú eré hbo tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ the comeback 2005 ó farahàn nínú àw...
liam neeson william john neeson born 7 june 1952 jẹ́ òṣèré ọmọ orilẹ̀-èdè northern ireland ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ oríyìn bi àmì-ẹ̀yẹ golden globe awards mẹ́ta àti tony awards méjì ní ọdún 2020 ó jẹ́ ipò keje nínú àwọn òṣèré tí the irish times so wípé ó gbajúmọ̀ jùlọ wọ́n fún neeson ní ipò officer of the order of the briti...
mark strong mark strong orúkọ àbísọ rẹ̀ ni marco giuseppe salussoliatí a bí ní ọjọ́ kàrún-ún oṣù kẹjọ ọdún 1963 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè britian tí ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi prince septimus ní stardust 2007 archibald ní rocknrolla 2008 lord henry blackwood nínú sherlock holmes 2009 frank d'amico nínú kick-ass 20...
temuera morrison temuera derek morrison tí a bí ní ọjọ́ kẹríndínlógbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1960 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè new zealand tí ó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀ èdè fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi dr hone ropata nínú eré shortland street ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi jake the muss heke nínú eré once were warriors tí ó jáde ní ọdún 1994 àti what be...
carla gugino carla gugino tí a bí ní ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1971 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orilẹ-èdè amẹ́ríkà lẹ́yìn ìgbà tí ó farahàn nínú eré troop beverly hills 1989 àti this boy's life 1993 ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ingrid cortez nínú eré spy kids 20012003 rebecca hutman nínú night at the museum 2006 la...
yusuf lule yusuf kironde lule 10 april 1912 21 january 1985 fìgbà kan jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti orílẹ̀-èdè uganda àti òṣìṣẹ́ ìjọba tó sìn gẹ́gẹ́ bí i ààrẹ uganda kẹrin láàárín oṣù kẹrin àti oṣù kẹfà ọdún ìgbésí ayé rẹ̀ wọ́n bí yusuf lule ní 10 aprilm ọdún 1912 ní kampala ó kàwé ní king's college budo 192934 makerere university...
juan o'donojú juan de o'donojú y o'ryan tí a bí ní ọjọ́ 30 oṣù july ọdún 1762 tó sì ṣaláìsí ní ọjọ́ 8 oṣù october ọdún 1821 jẹ́ ológun ọmọ ilẹ̀ spain tó tu n jẹ́ òun sì ni viceroy ilẹ̀ spain tó kẹ́yìn láti ọjọ́ 21 oṣù july ọdún 1821 wọ ọjọ́ 28 oṣù september ọdún 1821 lásìkò ogun òmìnira ti mexico
agustín de iturbide agustín de iturbide 27 september 1783 19 july 1824 tí orúkọ rẹ̀ ní kíkún jẹ́ agustín cosme damián de iturbide y arámburu tí wọ́n padà pè ní emperor agustín i of mexico jẹ́ ológun ti ilẹ̀ spain wọ́n fi iturbide sípò ààrẹ ní ọdún 1821 òun lo ṣẹ̀dá àsíá ti ìlú mexico
josé mariano michelena josé mariano michelena july 14 1772 may 10 1852 jẹ́ ààrẹ ìlú mexico tẹ́lẹ̀ rí láti oṣù kẹrin ọdún 1823 wọ oṣù kẹwàá ọdún 1824
miguel domínguez josé miguel domínguez alemán january 14 1756 most likely in mexico city april 22 1830 in mexico city jẹ́ ológun ti ilẹ̀ spain tó kó ipa ribiribi nínú ìgbòmìnira i ̀lú náà ó ti fìgbà kan darí ìlú spain
tunde olukotun oyekunle ayinde kunle olukotun jẹ́ ọmọ britain tó tún tan mọ́ ilẹ̀ nàìjíríà jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ tó sì tún jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti cadence design systems professor ní stanford school of engineering ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ electrical engineering àti computer science ní stanford university àti olùdarí láàbù stanford per...
winston wole soboyejo winston wole soboyejo tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí wole jẹ́ onímọ̀ sáyẹ́ǹsì ti orílẹ̀-èdè america tí àwọn òbí rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ yorùbá ó ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọl iṣẹ́ lórí ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì òun ni adele wọn ní worcester polytechnic institute
deji akinwande nigerian-american professor of electrical and computer engineeringdeji akinwande jẹ́ ọmọ orílẹ̀ naijiria tó sì tún tan mọ́ ilẹ̀ america ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ electrical and computer engineering tó sì tún ní àsopọ̀ mọ́ materials science ní university of texas at austin ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti presidential ...
john dabiri john oluseun dabiri jẹ́ ọmọ naijiria tó tún tan mọ́ ilẹ̀ america ó jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ tó ń rí sí ọkọ̀ òfurufú òun sì ni ọ̀jọ̀gbọ́n alága ní california institute of technology caltech
alexander animalu alexander obiefoka enukora animalu tí a bí ní 28 august 1938 jẹ́ ọ̀mọ̀wé ti orílẹ̀-èdènaijiria tó sì jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n àgbà tí ìmọ̀ physics ní university of nigeria nsukka ó gboyè bsc london ma cantab àti phd ibadan fas nnom iom
lola eniola-adefeso omolola lola eniola-adefeso jẹ́ onímọ̀ chemical engineer àti ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ chemical engineering biomedical engineering àti macromolecular science àti engineering ní university of michigan eniola-adefeso jé ọ̀kan lára àwọ olùdásílẹ̀ àti onímọ̀ sáyéǹsì àgbà ní asalyxa bio she was going to atten...
ndubuisi ekekwe ndubuisi ekekwe tí a bí ní july 1975 jẹ́ oníṣòwò orílẹ̀-èdè naijiria òun ni olùdásílẹ̀ first atlantic semiconductors microelectronics ní ọdún 2020 ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn the guardian nigeria tò ó pọ̀ mọ́ ọ̀kan lára àwọn ọgọ́fà ọmọ nàìjíríà tó ń ṣịṣẹ́ ribiribi
unoma ndili okorafor unoma ndili okorafor jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ kọ̀m̀pútà àti oníṣòwò okorafor ṣe ìdásílẹ̀ working to advance african women ní ọdún 2007 waaw is a 501c not-for-profit which promotes stem education to african women èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ àìlérè lórí tó ń ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ètò-ẹ̀kọ́ àwọn obìnrin nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ ṣáy...
philip emeagwali philip emeagwali tí a bí ní 23 august 1954 jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti gordon bell prize ní 1989
latunde odeku elatunde odeku tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ emanuel olatunde alaba olanrewaju odeku ni a bí ní ọdún 1927 sí ìpínlẹ̀ èkó orílẹ̀-èdè naijiria tó sì ṣaláìsí ní ìlú london ní ọdún 1974 jẹ́ oníṣẹ́abẹtọpọlọ àkọ́kọ́ tó máa jẹ́ ọmọ nàìjíríà united states ni ó ti gbẹ̀kọ́ ó sì fi ìdì iṣẹ́ yìí sọlẹ̀ sí ilẹ̀ africa
chidi chike achebe chidi chike achebe tí a bí ní ọjọ́ 24 oṣù may ọdún 1967 jẹ́ oníṣègùn òun ni alagá àti olùdarí àgbà fún aide african integrated development enterprise òun ni ọmọ kẹta ti chinua achebe ìyẹn òǹkọ̀wé tó kọ àwọn ìwé bí i things fall apart 1958 no longer at ease 1960 àti arrow of god 1964
charles rotimi charles nohuoma rotimi tí wọ́n bí ní ọdún 1957 jẹ́ olùdarí àgbà ní national institutes of health nih ó ṣe ìdásílẹ̀ african society of human genetics ní ọdún 2003 rotimi kó ipa ribiribi nínú ìṣẹ̀dá human heredity and health in africa h3africa pẹ̀lú ìrànwọ́ nih àti wellcome trust wọ́n yàn án sínú ẹgbẹ́ nat...
olawale sulaiman nigerian philanthropist neurosurgeonprofessor olawale sulaiman mdphd frcsc con jẹ́ oníṣẹ́abẹtọpọlọ tó gba ẹ̀kọ́ ní canada àti america ó sì tún jẹ́ onímọ̀ àti oníṣegùn àgbà ní nigerian heritage òun sì ni olùdarí àgbà ní rnz global ltd èyí tí wọ́n ṣèdásílẹ̀ ní ọdún 2010 ní ọdún 2019 wọ́n yàn án sípò olùd...
segun toyin dawodu segun toyin dawodu tí wọ́n bí ní ọjọ́ 13 oṣù october ọdún 1960 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiriató sì jẹ́ oníṣègùn àrùn-ọpọlọ àti agbẹjọ́rò pẹ̀lú wellspan health ó ṣịṣẹ́ bí i ọ̀jọ̀gbọ́n pẹ̀lú albany medical college
samuel dagogo-jack samuel e dagogo-jack jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria tó sì tún tan mọ́ ìlú american ó jẹ́ oníṣègùn
obioma paul iwuanyanwu obioma paul iwuanyanwu tí wọ́n bí ní ọdún 1962 tí orúkọ rè ní kúkurú sì jẹ́ obiwu jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú america ó jẹ́ òǹkòwé àti ọ̀jọ̀gbọ́n ó jẹ́ olùkọ́ àgbà ní central state university
wendy osefo wendy onyinye osefo tí wọ́n bí ní may 21 1984 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú america ó jẹ́ sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ sí ètò òṣèlú àti gbajúmọ̀ orí èrọ̀-amóhùnmáwòrán ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní johns hopkins school of education ó ṣàfihàn nínú fíìmù àgbéléwò the real housewives of potomac
kalu ndukwe kalu kalu ndukwe kalu jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú america tó jẹ́ oníṣẹ́ tó ń rí sí ọ̀rọ̀ òṣèlú ó sì tún jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n tó ń kọ́ political science àti national security policy ní auburn university montgomery àti ọ̀jọ̀gbọ́n ní university of tampere finland
saheed aderinto saheed aderinto tí wọ́n bí ní january 22 1979 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú america ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n tó ń kọ́ history and african and african diaspora studies ni florida international university bákan náà ló jẹ́ òǹkọ̀wé tó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmi-ẹ̀yẹ òun ni olùṣẹ̀dásílẹ̀ lagos studies associ...
elechukwu njaka mazi elechukwu nnadibuagha njaka 23 june 1921 14 january 1975 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria àti onímọ̀ ọ̀rọ̀ òṣèlú ó gbajúmọ̀ fún ìwé rẹ̀ igbo political culture
olu oguibe olu oguibe tí wọ́n bí ní14 october 1964 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú america ó jẹ́ ayàwòrán àti onímọ̀ ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní university of connecticut storrs ó sì tún jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ àgbà ní vera list center for art and politics ní new york city àti smithsonian institution ní washington dc
nkechi agwu nkechi madonna adeleine agwu tí wọ́n bí ní october 8 1962 jẹ́ olùkọ́ ẹ̀kọ́ ìṣirò ní borough of manhattan community college èyí tó jẹ́ apá kan ti city university of new york
abba gumel abba gumel jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n tó ń kọ́ ẹ̀kọ́ ìṣirò ní university of maryland college park iṣẹ́-ìwádìí rẹ̀ dálé lórí ètò ìṣirò gumel fìgbà kan kọ́ ìṣirò ní arizona state university kí ó tó di alága the michael and eugenia brin endowed e-nnovate ní university of maryland college park ní ọdún 2022
benjamin akande benjamin ola akande jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú america tó sì tún jẹ́ onímọ̀ ọ̀jọ̀gbọ́n àti oníṣòwò ńlá ní oṣù may ọdún 2021 wọ́n fi sípò ìgbá-kejì ààrẹ director human resources head of diversity and inclusion stifel financial èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìfowópamọ́ tó ń rí sí ìdókòwò òun ni ààrẹ ...
joseph abiodun balogun joseph abiodun balogun fas tí wọ́n bí ní january 1 1955 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú america tó jẹ́ onímọ̀ àti ọ̀jọ̀gbọ́n ní college of health sciences ní chicago state university illinois àti university of medical sciences ní ipinle ondo nàìjíríà ó wà nípò díìnì college of health s...
johnson o akinleye johnson o akinleye jẹ́ olórí-ẹ̀kọ́-gíga kejìlá ti north carolina central university wọ́n yàn án sípò yìí ní ọjọ́ 26 oṣù june ọdún 2017
okwui enwezor okwui enwezor 23 october 1963 15 march 2019 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó jẹ́ olùtọ́jú mùsíọ́ọ̀mù aṣàríwísí sí iṣẹ́-ọnà òǹkọ̀wé akéwì àti onímọ̀ ó fìgbà kan gbéní new york city àti munich ní ọdún 2014 wọ́n tò ó pọl mọ́ ọgọ́rùn-ún àwọn ènìyàn tó ń ṣịṣẹ́ ọnà
opeoluwa sotonwa opeoluwa sotonwa tí wọ́n bí ní ijebu-ode jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú america arákùnrin yìí jẹ́ agbẹjọ́rò fún àwọn odi ajàfẹ́tọ̀ọ́ àwọn odi àti òǹkọ̀wé ìwé lítíréṣọ̀ ní oṣù february ọdún 2021 gómínà charles baker yàn án sípò kọmíṣọ́nà àti olórí massachusetts commission fún àwọn odi kí wọ́...
ayọ tometi ayọ tometi tí wọ́n bí ní august 15 1984 tó fìgbà kan jẹ́ opal tometi jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú america ó jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn òǹkọlwé àti olùṣètò ìlú ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùṣèdásílẹ̀ black lives matter blm ó sì fìgbà kan jẹ́ olùdarí àgbà black alliance for just immigration baji níbi tó...
john o agwunobi john o agwunobi jẹ́ ọmọ scotland tó sì tún tan mọ́ orílẹl-èdè nàìjíríà tó jẹ́ oníṣègùn àwọn ọmọdé ó sì fìgbà kan jẹ́ adarí agbà àti alága herbalife nutrition òun sì ni igbákejì ààrẹ ti walmart àti ààrẹ retailer health and wellness business láti ọdún 2007 wọ 2014
tayo oviosu tayo oviosu jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú america tó jẹ́ oníṣòwò tó tún ṣèdásílẹ̀ paga èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tó fàyè gba sísan owó láti orí ẹ̀rọ-alágbèéká wa orílẹ̀-èdè nàìjíríà ni paga kọ́kọ́ gbòde
adebayo alonge adebayo alonge jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria tó jẹ́ olóògùn àti oníṣòwò òun ló jáwé olúborí fún ìdíje tí ọdún 2019 ti hello tomorrow global deeptech challenge èyí tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí bnp paribas group deep tech award ó gba àmì-èyẹ yìí látàri irinṣẹ́ kan tó lè ṣàwárí oògùn ẹbu tí ó ṣẹ̀dá ó jẹ́ ọ̀kan lára ...
tiffany trump tiffany ariana trump tí wọ́n bí ní october 13 1993 jẹ́ ọmọ kẹrin ti ààrẹ us ìgbà kan èyí tí í ṣe donald trump tiffany sì ni ọmọ kan ṣoṣo tí ìyàwó kejì donald bí
patrick wilson patrick joseph wilson tí a bí ní ọjọ́ kẹta oṣù keje ọdún 1973 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi òṣèré ní ọdún 1995 nígbà tí ó ṣeré nínú broadway musicals wọ́n yán mọ́ ara àwọn tí ó tó sí tony awards ní ẹ̀mejì fún ipa nínú eré the full monty 20002001 àti oklahoma 2002 ó tún ṣer...
ken watanabe ken watanabe 渡辺 謙 tí a bí ní ọjọ́ kanlélógún oṣù kẹ̀wá ọdún 1959 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè japan ó gbajúmọ̀ láàrin àwọn elédè gẹ̀ẹ́sì fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí general tadamichi kuribayashi nínú eré letters from iwo jima àti gẹ́gẹ́ bi lord katsumoto moritsugu nínú eré the last samurai èyí tí ó mú kí wọ́n yán kú...
adebayo ogunlesi adebayo bayo o ogunlesi con tí a bí ni december 20 1953 jẹ́ agbẹjọ́rò àti oní-ìdókòwò ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria òun ni olùdarí àgbà fún global infrastructure partners gip ogunlesi fìgbà kan jẹ́ olórí wọn ni credit suisse first boston kí wọ́n tó yàn án sípò alága
maya horgan famodu maya horgan famodu jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú america tó jẹ́ oníṣòwò àti olùdásílẹ̀ ingressive ó ṣèdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ kan tí orúkọ rẹ̀ n jẹ́ high growth africa summit àti tech meets entertainment summit maya pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ sean burrowes àti blessing abeng tún ṣe ìdásílẹ̀ ingress...
magnus l kpakol magnus lekara kpakol ni adarí àgbà àti alága fún economic and business strategies ìyẹn ilé-iṣẹ́ tó ní ẹ̀ka iṣẹ́ ní ìlú òyìnbó àti orílẹ̀-ède nàìjíríà ó jẹ́ olùdarí àgbà àti akọ́nímọ̀ọ́ṣòwò ní economic and business strategies ltd ní ọdún 2001 ààrẹ olúṣẹ́gun ọbásanjọ́ yàn án sípò olùdámọ̀ràn fún ọ̀rọ̀ ajé
angelica nwandu angelica nwandu tí wọ́n bí ní may 10 1990 ni olùdásílẹ̀ the shade room tsr èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ orí ẹ̀rọ-ayélujára tó níṣe pẹ̀lú ṣíṣe òfófó àwọn gbajúmọ̀ iye àwọn ènìyàn tó ń wo ètò yìí ń lọ bí i 20 million ní ọdún 2016the new york times to the shade room sábẹ́ àwọn ètò tó gbajúmọl jù lọ ní orí ẹ̀rọ-ayél...
yinka faleti adeyinka faleti tí wọ́n bí ní june 20 1976 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú america tó jẹ́ olúṣèlú àti ológun fún ìlú america ó gboyè bachelor of science láti united states military academy ní west point àti juris doctor láti washington university in st louis
oye owolewa adeoye oye owolewa tí wọ́n bí ní ọdún 1989 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú america tó jẹ́ olóṣèlú olóògùn àti ọmọ-ẹgbẹ́ democratic party ní oṣù november ọdún 2020 wọ́n yàn án sípò ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ti orílẹ̀-èdè america
ochai agbaji ochai young agbaji tí a bí ní april 20 2000 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rè fún utah jazz èyí tó jẹ́ ti national basketball association nba gẹ́gẹ́ bí i ọ̀gá àgbà ní university of kansas wọ́n fún agbaji lórúkọ wọ́n sì dìbò fun ní ọdún 2022 gẹ́gẹ́ bí i big 12 player of the year ó darí ẹgbẹ́ jayhawks nínú ìdíje títí...
suleiman braimoh suleiman okhaifoede braimoh jr tí a bí ní october 19 1989 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó tan mọ́ ìlu america ó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsápẹ̀rẹ̀ tó gbá bọ́ọ̀lù fún maccabi tel aviv èyí tí í ṣe ti israeli basketball premier league àti euroleague ó tún gbábọ́ọllù fún ilé-ìwé gíga ti rice university kí ó tó b...
chamberlain oguchi chamberlain champ nnaemeka oguchi tí a bí ní april 28 1986 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè naijiria tó tan mọ́ ìlú america tó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsápẹ̀rẹ̀ tó gbá bọ́ọ̀lù náà fún boulazac basket dordogne ti lnb pro b orúkọ rẹ̀ emeka jẹ́ àgékúrú orúkọ igbo rẹ̀ tí ń ṣe chukwuemeka tí ìtumọ̀ rẹ̀ jẹ́ ọlọ́run ti ṣeun ...
john malkovich john malkovich tí a bí ní ọjọ́ kẹsán oṣù kejìlá ọdún 1953 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ àwọn bi primetime emmy award wọ́n sì ti yán mọ́ àwọn tí ó tó sí àmì-ẹ̀yẹ academy awards lémejì bafta award screen actors guild awards àti àmì ẹyẹ golden globe awards lẹ́meta malkovich ...
mark hamill mark richard hamill tí a bí ní ọjọ́ karúndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1951 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà àti olùkọ̀wé ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi luke skywalker nínú àwọn eré star wars ó bẹ̀rẹ̀ ní original 1977 film wọ́n sì fun ní àmì ẹ̀yẹ saturn mẹ́ta fún ipa rẹ̀ nínú the empire strikes back 1980...
harrison ford harrison ford tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje ọdún 1942 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ó ti farahàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré ọ̀pọ̀ sì mọ́ sí cultural icon orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà àwọn eré tí ó ti ṣeré ti pa tó iye owó tí ó lé ní bílíọ́nù márùn-ún dọ́là ní àríwá amẹ́ríkà àti iye tí ó lé ní bílíọ́nù mẹ́sán dọ́là ...
anthony daniels anthony daniels tí a bí ní ọjọ́ kanlélógún oṣù kejì ọdún 1946 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè britain tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ fún ipa gẹ́gẹ́ bi c-3po nínú eré star wars mẹ́wàá daniels ni ó fọ ohùn fún legolas nínú eré ralph bakshi bẹ̀bí tí wọ́n ṣe fún the lord of the rings 1978 ó ti farahàn nínú àwọn britain kọ̀kan ...
crystal clarke crystal clarke tí a bí ní ọdún 1993 tàbí ọdún 1994 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ọ̀pọ̀ mọ́ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi tina argyll nínú eré bbc àti amazon prime tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ ordeal by innocence 2018 àti gẹ́gẹ́ bi georgiana lambe nínú eré itv àti pbs tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ sanditon 2019 ìpìlẹ̀ wọ́n bí clark...
billie lourd billie catherine lourd tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gún oṣù keje ọdún 1992 jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orilẹ̀-èdè amẹ́ríkà ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi l chanel #3 nínú eré fox tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ scream queens 20152016 àti ipa rẹ̀ nínú fx tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ american horror story 2017títí di ìsinsìnyí ó farahàn gẹ́gẹ́...
judah friedlander judah friedlander tí a bí ní ọjọ́ kẹríndínlógún oṣù kẹta ọdún 1969 jẹ́ òṣèré àti aláwadà ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi akọ̀wé frank rossitano nínú nbc sitcom 30 rock friedlander tún gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi toby radloff nínú eré american splendor ipa tí ó mú kí ọ̀pọ̀lọ...
thomas brodie-sangster thomas brodie-sangster tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1990 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè britain ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi sam love actually 2003 simon nínú nanny mcphee 2005 ferb nínú phineas and ferb 20072015 jojen reed nínú game of thrones 20132014 newt nínú maze runner film ...
ilaje ìlàje jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ tó wà ní ìpínlẹ̀ òndó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà olú-ìlú náà wà ní igbokoda ẹ̀yà yorùbá yìí dá yàtọ̀ nínú èdè ẹnu wọn àkójọpọ̀ ìlú bí i ondo ogun àti delta ló bí ìlú yìí
ada ada jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìlú tó wà ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ boripe ní ipinle osun ní orílẹ̀-èdè naijiria oba oyetunde olumuyiwa ojo the olona of ada ni olórí ìlú náàlára àọn ọjà tó wà ní ìlú náà ni ile oba oludele ile oba adeitan ile oba olugbogbo ile aro ile alagbaa ojomu oteniola alade eesa jagun osolo oke baale as...