raw_text
stringlengths
2
128k
abacha oúnjẹ nigerian food abacha jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ounjẹ ẹ̀yà igbos ní guusu apá ìlà oòrùn nàìjíríà
kunu kunu ti a tun mọ si kununzaki jẹ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìkan mimu ti o gbajumọ kakiri orílè-èdè naijiria pupọ julọ ni àríwá naijiria wọn má ń sábà fi jéró tàbí ọkà se nígbà míràn wón ó lọ àgbàdo wọ́n ma ń se nípa rí rẹ jéró tàbí ọkà tí ó ti gbó sí omi fún ìjọ́ díè tí won ó sì lọ̀ ọ́ mọ́ odukwu atalẹ tàbí ata
banga soup banga rice jẹ́ ọ̀kan lára àwọn iresi ní nàìjíríà tí wón fi eyín àti ọbẹ̀ ẹ̀yìn se àwọn ẹ̀yà urhobo ní apa gúúsù nàìjíríà ni wọ́n má ń sábà sè é banga túmọ̀ sí omi tí wọ́n ba yọ lára eyìn wọ́n ń pe ní iresi banga nítorí bí wọ́n bá ti fún omi jáde lara eyìn tán wọ́n ó fi se iresi àwọn ẹ̀yà urhobo kì í fi èròjà...
ẹran ìgbẹ́ meat hunted in tropical forests ẹran ìgbẹ́ túmọ̀ s'àwọn ẹran tí wọ́n pa ní inú igbó ó sì tún túmọ̀ sí àwọn ẹranko tí àwọn ènìyàn ń jẹ nínú igbó pàá pàá jù lọ ní ilẹ̀ adáwọ̀ ẹran ìgbẹ́ jẹ́ orísun amú purotéènì ara fún àwọn ènìyàn latin amẹ́ríkà àti asia ó tún jé orísun oúnjẹ fún àwọn ẹlòmíràn pàá pàá jùlo àwọ...
emmy gee emmanuel nwankwo tí a tún mọ̀ sí emmy gee jẹ́ olórin ilẹ̀ nàìjíríà tó ń gbé ní orílẹ̀-èdè south africa orin àdákọ àkọ́kọ́ rẹ̀ rands and nairas wà nípò keje láàárín àwọn orin orí àtẹ ní ilẹ̀ south africa ó bẹ̀rẹ̀ sí ní gba orin sílẹ̀ nígbà tó wà ní ọmọdún mẹ́rìndínlógún ó sì í ṣiṣẹ́ pẹ̀lú shizzi n ọdún 2004 ó j...
amarachi amarachi uyanne wọ́n bí ní 17 oṣù kèje 2004 ó gbajúgbajà gẹ́gẹ́ bí i amarachi ó jẹ́ ọmọdé-ọ̀dọ́ olórin nàìjíríà oníjó a sì tún mọ̀ ọ́ fún ìlò irinṣẹ́ violin rẹ̀ ọ̀pọ̀ ènìyàn ló mọ̀ ọ́ gẹ́gẹ́ bí i olúborí ìdíje naigeria's got talent tí àwọn ọ̀dọ́ ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ amarachi jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ dẹ́ltà wọn tọ dàgbà ní ìpí...
ìrẹsì jọ̀lọ́ọ̀fù ìrẹsì aláṣẹ̀pọ̀ jọ̀lọ́ọ̀fù jẹ́ ìrẹsì àsèpọ̀ láti ìwọ̀-oòrùn áfíríkà oúnjẹ yìí jẹ́ àdàpọ̀ ìrẹsì tòmátì àlùbọ́sà àwọn èròjà amóúnjẹ-ta-sánsán ẹ̀fọ́ àti ẹran papọ́ sínú ìkòkò kàn pẹ̀lú èròjà àti pé orísirísi ònà ní àwọn èèyàn ń gbà ṣe oúnjẹ yìí níbikíbi ìtàn àti ìpìlẹ̀ṣẹ̀ wọ́n tọ orírun ìrẹsì àsèpọ̀ jọ̀lọ...
bilkisu labaran nigerian journalist bilkisu labaran jẹ́ oniroyin ní orílẹ̀ èdè naijiria òun sì ni olórí èka bbc lórí ìròyìn àti nkan tí ó ń ṣẹlẹ̀ ni afrika ó kópa púpò nínú ìdá bbc pidgin òun sì ni oootu àkọ́kọ́ fún bbc pidgin ó wà lára àwọn alamojuto bbc africa eye documentaries kí ó tó dára pò mọ́ bbc ó jé olùkọ́ ní ...
ọlamide tòyin àdèbàyọ
abel olúwáfẹ́mi dòsùmú
fọlákẹ́ ọ̀náyẹmí
balógun yakub abíọ́dún
seyi adisa ṣeyi joseph adisa tí a bí ni ọjọ́ keje oṣù kọkànlá ọdún 1983 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà agbẹjọro ati oloṣelu ni ó sì tún jẹ́ olókoòwò agbẹnusọ àti alabojuto ni ile iṣẹ ijọba ó ti fi ìgbà kan jẹ́ akọ̀wé agba fún gómìnà nigba kan ri ni ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ sẹ́nétọ̀ abiola ajimobi ní akoko yi ó jẹ́ ọmọ ile igbimọ aṣo...
ọjọ́rú
ṣèyí àdìsá
ọọ̀ni ife
aláàfin <ns>0</ns> <revision> <timestamp>2022-10-22t131626z</timestamp> <contributor> <username>ọmọladéabídèmí99</username> </contributor> <comment>ọmọladéabídèmí99 ṣeyípòdà ojúewé aláàfin sí aláàfin ìlú ọ̀yọ́</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format>
tẹ́tẹ́ ní nàìjíríà tẹ́tẹ́ ní nàìjíríà kò ní ìmójútó tó dára bótilẹ̀ jẹ́ pé òfin wà nípa tẹ́tẹ́ ọ̀pọ̀ àwọn ilé kàlòkàlò kàsínò tó wà ní nàìjíríà kò ní ìwé-àṣe látọwọ́ ìjọba the federal palace hotel ní ìlú èkó ni kàsínò tó tóbi jùlọ ní nàìjíríà wà
jollof rice
arese ugwu arese ugwu tí wón bí ní march 19 1986 jẹ́ olùkọ̀wé àti olùṣe filmu ọmọ orílè-èdè nàìjíríà ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn mọ arese sí smart money arese orúkọ tí wọ́n fun nítorí filmu rẹ̀ smart money woman àti ilé-isé rẹ̀ smart money africa ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí arese sí inú ìdílé victor àti funke ogiemwonyi...
cdq sodiq abubakar yusuf ìbí jẹ́ may 6 1985 ẹni tí ayé mọ sí cdq jẹ́ olórin ọ̀kọrin tí ó jẹ́ gbajù gbajà jẹ́ ọmọ bíbí ike nàìjíría tí ó kọ nọwọ́ sókè tí olorin wizkid náà kópa nínú orin náà àti ọlámide tí ì wá lábẹ masterkraft nígbà kàn rí o maa ń lo ohun èlò orin ki ó tó sún sí orin tí jé kí ó gbà àmi ẹ̀yẹ ní ọdún 201...
micheal taiwo akinkunmi micheal táíwò akínkúnmi ofr tí wọ́n bí ni ọjọ́ kẹwàá oṣù karùn-ún ọdún 1936jẹ́ gbajúgbajà òṣìṣẹ́ se fẹ̀yìntì omo orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó dìsáínì fúlàgì àpapọ̀ orílẹ̀-èdè nàìjíríàìnagijẹ rẹ̀ ni ọ̀gbẹ́ni fúlàgì ìgbésí ayé ati iṣẹ́ rẹ̀ akínkúnmi jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ìbàdànẹ̀yà yorùbá ọmọtáyéwò àgbà ìbej...
2007 nigerian general election ìdìbò gbogbogbòò ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà ni ọdún 2007 láti yan olórí orílẹ̀ ede ati ọmọ ilé ìgbìmò asòfin àpapọ̀ wáyé ni ọjọ́ kọkànlélógun oṣù kerin ọdún 2007 àgbétẹ́lẹ̀ ní ọjọ́ kẹrindínlógún oṣù karùn-ún ọdún 2006 àwọn ilé ìgbìmò asòfin dibò láti ṣe àtúnṣe ìwé òfin pé kí olórí orílẹ̀ èdè ...
ìdìbò gbogbogbòò orílẹ̀ èdè nàìjíríà ní ọdún 2007 ìdìbò gbogbogbòò ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà ni ọdún 2007 láti yan olórí orílẹ̀ ede ati ọmọ ilé ìgbìmò asòfin àpapọ̀ wáyé ni ọjọ́ kọkànlélógun oṣù kerin ọdún 2007 ìdìbò gómìnà àti ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ti wáyé ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kerin náà ìdìbò gómìnà àti ilé ìgbìmọ̀ ìpínl...
oluyemi oluyemi ni oruko yorùbá naijiria itumo oluyemi ni olorun fun mi ni itelorun awọn eniyan olokiki pẹlu orukọ akọkọ/fifun pẹlu
aníkúlápó nigerian film aníkúlápó jẹ́ fíìmù onítàn àròsọ nàìjíríà ọdún 2022 tí kúnlé afọláyan ṣe tí netflix sì pín kiri wọ́n gbé e jáde lọ́jọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 2022 àwọn òṣèré hakeem kae-kazim ṣọlá ṣóbọ̀wálé kúnlé rẹmí bím̀bọ́ adémóyè ati táíwò hassan ló kó ipa aṣáájú ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ni wọn ya eré afọláyan sì ti ...
jim iyke 2012 nigerian disaster thriller film last flight to abuja jẹ́ eré ti ọdún 2012 ti ilẹ̀ nàìjíríàgerian disaster thriller film written by tunde babalola directed and produced by obi emelonye and starring omotola jalade ekeinde hakeem kae-kazim and jim iyke shot in lagos the film received 5 nominations at the 201...
strikex cryptocurrency exchange and blockchain-based company tradestrike bvi is a cryptocurrency and blockchain financial services company based in the british virgin islands and london united kingdom the company began by launching a cryptocurrency token built on the binance smart chain in 2021 and has since created mu...
eduardo riedel eduardo riedel 5 keje 1969 jẹ oloselu ara ilu brazil ati oniṣowo ti o somọ si ẹgbẹ tiwantiwa awujọ ti ilu brazil jẹ gomina ti mato grosso do sul ni awọn idibo 2022 ni brazil tẹlẹ ti di ipo ti akowe ti ipinle fun awọn amayederun ti mato grosso do sul lati kínní 22 2022 si oṣu kini ọjọ 1 ọdun 2023 ni ọdun ...
université paris cité yunifásítì paris cité tabi yunifasiti paris cité ile-ẹkọ giga ti gbogbo eniyan ni ilu paris faranse o ṣẹda ni ọdun 2019 nipasẹ apapọ ti université paris descartes ati université paris-diderot ile-ẹkọ giga naa ni awọn ẹka mẹta
awọn gypsies gypsies jẹ ẹya kan lati india ti o ngbe ni akọkọ ni yuroopu yi ni a kukuru article jọwọ mu yi
vyborg
chuma mmeka chuma mmeka ti a tun pè ni 't-char' jẹ óṣèrè lọkunrin ti nollywood arakunrin naa tun jẹ ólukọwè ati ẹni to fẹran lati ma ran awọn ọmọdè lọwọ igbèsi àyè àrakunrin naa chuma ni a bini ọjọ kejileelógun óṣu june ni ọdun 1975 fun enyi jim i mmeka ati lolo jossy c ni amaigbo ni ijọba ibilẹ ti nwangele ni ipinlẹ i...
akpororo bowoto jephthah oluwatiseyifumi tanimola ti inagijẹ rẹ njẹ akpororo jẹ alawada ati óṣèrè lọkunrin ilẹ naigiria igbèsi àyè àràkunrin naa akpororo ni a bi tosi dagba si warri ni ipinlẹ delta ṣugbọn to wa lati ilajẹ ipinlẹ ondo irin ajo arakunrin naa bẹrẹ gẹgẹbi ólórin ni ọdun 2008 nibi to ti pegede ninu idije zo...
chuks d general chuks d general ti órukọ a bisọ rẹ njẹ chukwuyem jude israel jẹ alawada host radio presenter ati óṣèrè lọkunrin arakunrin naa gbajumọ lori awọn awada rẹ chuks jẹ óludari show ti awada to kó awọn gbajumọ ilẹ naigiria jọ lori idanilaraya chuks ni ójẹ alawada to pègèdè julọ ni abuja óṣèrè lọkunrin naa da o...
ààlọ́ ìjàpá asín àti ọ̀kẹ́rẹ́ ààlọ́ ìjàpá asín àti ọ̀kẹ́rẹ́ ààlọ́ ìjàpá asín àti ọ̀kẹ́rẹ́ ààlo oooo ààlọ́ o elegbe ààlọ́ apààlọ ààlọ́ mi dá firi gbàgbó lori ìjàpá asín àti ọ̀kẹ́rẹ́ ni ayé àtijó ọ̀kẹ́rẹ́ àti ìjàpá jẹ́ ọ̀rẹ́ ẹ kò-rí-kò- sùn wón fẹ́ràn ara wọn lópòlọpò òwò kan náà ni wọ́n jo ń se àwo ni wọ́n ń tà ibi kan ...
ìjàpá l’óyun ijángbòn ààlọ́ ìjàpá àti yannibo aya rẹ ààlo ó ààlò ààlọ́ mi dá fìrìgbagbò ó dá lórí ìjàpá àti yánníbo aya rẹ ìjàpá fẹ́ ìyàwó rẹ̀ nígbàtí ó pé ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dọ́gbọn orúkọ rẹ̀ a maa jẹ́ yánníbo yánníbo rẹwá pupọ l’óbìnrin ó pupa fòò eyín ẹnu rẹ̀ funfun nigín nigín dada iyàwó ìjàpá singbọnlẹ̀ kò sí ohun ti o...
obafemi lasode ọbáfẹ́mi lásọdé tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrin oṣù kejìlá ọdún 4 1955 jẹ́ gbajúmọ̀ olórin olùdarí àti olóòtú sinimá ó jẹ́ oǹkọ̀wé àti olóòtú orin eré-oníṣe ọmọ nigeria òun ni olùdarí-àgbà ilé-iṣẹ́ even-ezra nigeria limited tí ó ṣe agbátẹrù sinimá olókìkí nì sango tí ó gba ọ̀pọ̀ àmì-ẹ̀yẹ lọ́dún 1997 ìgbésí-ayé r...
adegboyega dosunmu amororo ii adegboyega dosunmu amororo ii con jẹ́ ọba ilẹ̀ òwu ní ipinlẹ ogun ní orílẹ̀-èdè naijiria à-pè-jálẹ̀ oyè rẹ̀ ni olowu ti ilẹ owu ó gun orí oyè yìí nígbà tí ọba olawale adisa odeleye lagbedu i wàjà ní oṣù kẹfà ọdún 2003 ní ẹni ọdún márùn-dín-láàádọ́rin ọba adegboyega dosunmu jẹ́ ọmọ bíbí inú...
ademola adeleke ademola nurudeen jackson adeleke ojoibi 13 may 1960 je oloselu ati onisowo naijiria kan eni ti o ti se gomina ipinle osun lati odun 2022 òun ni seneto tó sójú agbègbè senatorial osun-west lati 2017 si 2019 o wà lati ìdílé adeleke ti ede ni ipinle osun o dije nínú idibo gomina ipinle osun lodun 2022 labẹ...
teju babyface nigerian comedian teju babyface ni tun pè ni gbadewonuola olateju oyelakin to jẹ alawada ati ólukọwè ilẹ naigiria awọn ọmọ órilẹ ede naigiria ma n pè arakunrin naa ni oba sọrọsọrọ igbèsi àyè àrakunrin naa teju babyface ni a bini ọjọ ogun óṣu january ọdun 1979 ni ọdun 1999 arakunrin naa bẹre irinajo iṣẹ rẹ...
aalo ìjàpá àti aparo ààló o ààlọ ààló mi dá fìrìgbagbó ó dá lórí ìjàpá àti àparò
go dog go go dog go jẹ jara ti ere idaraya ará amẹ́ríkà-kánádà
haley lu richardson haley lu richardson ti a bi ni 7 march 1995 jẹ oṣere ara ilu amẹrika kan ni atẹle awọn ipa tẹlifisiọnu ni kutukutu lori disney channel sitcom shake it up 2013 ati eré elere abc family ravenswood 2013 2014 o ṣe ni fiimu ti n bọ ti ọjọ-ori the edge of seventeen 2016 ati fiimu ibanilẹru ọpọlọ pipin 201...
5460 tsénaatʼaʼí 5460 tsénaatʼaʼí jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
7060 al-ʻijliya 7060 al-ʻijliya jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
aalo ìjàpá àti ọmọ òrùkan meta ààlọ́ oooo ààlò ààlọ́ mi dá firigbagbo ó dá lórí ìjàpá àti àwọn ọmọ òrukàn mẹ́ta kan ní ìgbà láéláé àwọn ọmọ òrukàn mẹ́ta kan wà tí orúkọ wọn ní jẹ́ otarún akọpe àti awẹkun àwọn ọmọ yìí pinnu láti bẹ̀rẹ̀ isẹ owó láti ìgbà tí òbí àwọn ọmọ yìí tí kú ìjàpá máa ń tọju wọn ó sì máa ń gbà wọn n...
14566 hokuleʻa 14566 hokuleʻa jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
11027 astafʹev 11027 astafʹev jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
13474 vʹyus 13474 vʹyus jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
12979 evgalvasilʹev 12979 evgalvasilʹev jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
12219 grigorʹev 12219 grigorʹev jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
10718 samusʹ 10718 samusʹ jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
10261 nikdollezhalʹ 10261 nikdollezhalʹ jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
9154 kolʹtsovo 9154 kolʹtsovo jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
2922 dikanʹka 2922 dikanʹka jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
7725 selʹvinskij 7725 selʹvinskij jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
ìfáàrà lórí ààlọ́ ìfáàrà lórí àlọ́ ní ilẹ̀ yorùbá ní ìgbà tí kò tíì sí ètò mọ̀ọ́kọ-mọ̀ọ́kà tí ó wà lóde òní ọ̀rọ̀ àt'ẹnu dé ẹnu ni àwọn bàbá ńlá wa máa n fi ń ṣe àkọsílẹ̀ àwon ìṣẹ̀lẹ̀ ti o bá ṣẹ̀ wọn a máa fi irú ìtàn tí wọn bá lẹnu àwọn baba wọn yìí fún ìran tí ó bá tẹle won fún àpẹẹrẹ àwọn bàbá yóò sọ ìtàn fún àwọn ọ...
6755 solovʹyanenko 6755 solovʹyanenko jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
benedict okey oramah benedict okey oramah jẹ onimọ-ọrọ-aje ati oniṣowo lorilẹ-ede naijiria o si ti jẹ ààrẹ ati alaga igbimọ awọn oludari ti african exportimport bank afreximbank lati ọdun 2015 o ti ṣe atẹjade iwe kan awọn ipilẹ ti isuna iṣowo iṣeto o si ti kọ diẹ sii ju awọn nkan 35 lori ọpọlọpọ awọn ọrọ-aje iṣowo ati ...
ààlọ́ ìjàpá àgbò àti igbá apààlọ́ ààlọ́ o ègbè ààlọ́ ààlọ̀ apààlọ́ ààlọ́ mi dá fìrìgbagbóò ó dálérí ìjàpá tìrókò ọkọ yáńníbo tí ń lọ láárín ẹ̀pà tí ìpàkọ́ rẹ̀ ńhàn fìrìfìrì o ní ọpẹ́lopẹ́ pé òun ga ní àtijọ́ ní ìlú ìjàpá igbá títà lowó lórí àgbẹ̀ tí o bá gbin igbá ti di ọlọ́rọ̀ ìjàpá wo ara rẹ̀ títí lọ́jọ́ kan pé òun n...
sunday jack akpan
sundayjack akpan
ìjàpá àti àdàbà ààlọ́ oooooo ààlọ́ ààló yìí dá lórí ìjàpá àti ẹyẹ àdàbà gẹ́gẹ́ bí a se mọ pé alágàbàgebè ni ìjàpá olè àti ọkànjúwà ni pẹ̀lú ní ayé àtijó ìjàpá àti àdàbà jọ ń se ọ̀rẹ́ àdàbà ní ẹṣin kan tó máa ń gùn kiri tí ìjàpá kò sì ní nǹkankan ìjàpá ronú lọ́jọ́ kan ó sì gbèrò bí yóó ti se pa ẹṣin àdàbà ó rí pé àdàbà ...
ìjàpá lọ jẹun l'ọ̀dọ̀ ìyá ajá ààló ìjàpá àti ajá apààlọ́ ààlọ́ o agbe ààlọ́ ààlọ̀ apààlọ́ ààlọ́ mí dá gbà-á ó dá gbò-ó ó dá fìrìgbagbóò o dálérí ìjàpá àti ajá ní àtijọ́ ní ìlú ìjàpá ìyàn mú gan-an ní ìṣe àgbẹ̀ ni olúkúlùkù ń se àwọn ìyàwó kò ní ìṣe míràn àfi kí wọ́n tẹ̀le oko wọn lọ sóko fún ìrànlọ́wọ́ bí òjò kò bá ti ...
àlọ́ ìjàpá ìdí tí orí ìjàpá fi pá apààlọ́ ààlọ́ o ègbè ààlọ́ ààlọ̀ apààlọ ààlọ́ mí dá gbà-á ó dá gbò-ó ó dá fìrìgbagbóò o dálérí ìjàpá tó lọ jí ẹ̀bẹ ní ilé àná rẹ̀ ní ìgbà láíláí àbúrò ìyàwó ìjàpá kan fẹ́ gbé ìyàwó àwọn òbí ọkọ ìyàwó ti fi lé potí fọ̀nà rokà pe onílé àti àlejò wá síbi ayẹyẹ ìgbéyàwó aláririn náà yáńníb...
àlọ́ ìjàpá àti àlákàn apààlọ́ ààlọ́ o ègbè ààlọ́ ààlọ̀ apààlọ́ ààlọ́ mí dá gbà-á ó dá gbò-ó ó dá fìrìgbagbóò o dá lérí ìjàpá àti alákàn nígbà kan ìjàpá àti àlákàn ń ṣe ọ̀rẹ́ àlákàn ń gbé etí omi ó ń ṣiṣẹ́ pẹjapẹja ìjàpá ń ṣiṣẹ́ àgbẹ̀ ó ń gbé ibi tó jìnà s'omi èyi má ń jẹ́ kí ìjàpá tọrọ omi lọ́wọ́ àlákàn nígbà èérún tàb...
aalo ìjàpá àti aja ààlọ́ ìjàpá àti ajá ààlọ́ ooooo ààlò ààlọ́ mi dá firigbagbòó ó dá lórí ìjàpá àti aja ní ìlú kan ni ayé àtijó àwọn ẹranko méjì kan wà tí wọ́n jẹ́ ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ àwọn ọ̀rẹ́ méjì náà ni ìjàpátìrókò ọkọ yánníbo àti ajá iyàn mú púpọ̀ ní ìlú yìí débi wípé gbogbo igi wọ́wé tán àgbàdo kọ̀ kò gbó àwọn ọlọ́...
ààlọ́ ìjàpá àti àlákàn
ààlọ́ ìdí tí orí ìjàpá fi pá
ìjàpá kó gbogbo ọgbọ́n ayé sínú kèǹgbè apààlọ́ ààlọ́ o agbe ààlọ́ ààlọ̀ apààlọ́ ààlọ́ mí dá gbà-á ó dá gbò-ó ó dá fìrìgbagbóò o dálérí ìjàpá tìrókò ọkọ yáńníbo nígbà kan ìjàpá rò ó nínú ara rẹ̀ pé kí òun kó gbogbo ọgbọ́n ayé jọ pamó s'íbí kan kí òun wá di alákòóso rẹ̀ nitori ìjàpá je ẹranko to ni ọgbọ́n èwé oríṣiríṣi l...
ààlọ́ ìjàpá kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ àti adìẹ apààlọ́ ààlọ́ o agbe ààlọ́ ààlọ̀ apààlọ́ ààlọ́ mí dá gbà-á ó dá gbò-ó ó dá fìrìgbagbóò o dálérí ìjàpá tí ó fi ogbe orí àkùkọ fún kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ jẹ nígbà láíláí ìjàpá àti kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ jẹ́ ọ̀rẹ́ kòríkòsùn àwọn ẹranko kéékèèké ni kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ máa ń jẹ ìjàpá a máa bá àwọn ẹranko náà ṣeré lát...
aalo ìjàpá àti elédè ààlọ́ ooooo ààlọ ààlọ́ mi dá firigbagbòó ó dá lórí ìjàpá àti ẹlẹ́dẹ̀ ní ìgbà láíláí ìjàpá àti ẹlẹ́dẹ̀ jọ ńṣe ọ̀rẹ́ ní ọjọ́ kan ìjàpá lọ yá owó lọ́wọ́ ẹlẹ́dẹ̀ pẹ̀lú ìlérí pé títí ọjọ́ mẹ́ta ohun yíò dá owó yìí padà ṣùgbọ́n lẹ́hìn ọjọ́ mẹ́ta ìjàpá kò rí owó yìí dá padà fún ẹlẹ́dẹ̀ elédè bèèrè si para...
aalo asín ọ̀kẹ́rẹ́ àti ijapa ààlọ́ asín ọ̀kẹ́rẹ́ àti ìjàpá apá alo ààlo oooo elegbe ààlọ apààlọ ààlọ́ mi dá firi gbàgbó ó dá lori ìjàpá asín àti ọ̀kẹ́rẹ́ ni ayé àtijó ọ̀kẹ́rẹ́ àti ìjàpá jẹ́ ọ̀rẹ́ ẹ kò-rí-kò- sùn wón fẹ́ràn ara wọn lópòlọpò òwò kan náà ni wọ́n jo ń se àwo ni wọ́n ń tà ibi kan náà ni wọ́n sì pa àte sí on...
ọmọ ọlọ́run religious title god's son túndarí síbí yìí fún the 2002 nas album ẹ wo god's son album fún the 2014 film ẹ wo son of god film fún other uses ẹ wo son of god disambiguation ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ demigod tàbí son of heaven nínú ìtàn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olórí ni wọ́n ti fún ara wọn ní orúkọ bíi ọmọ ọlọ́run tàbí ...
bethlehem bethlehem lárúbáwá ‎ hébérù בֵּית לֶחֶם‎ jẹ́ ìlú ńlá kan tí ó wà ní orílẹ̀-èdè palestine ní apá ìwọ̀ oòrùn ìpínlẹ̀ tí ó tó kìlómítà mẹ́wá convert|10|km|mi|abbr=in}} sí ìlànà oòrùn jerusalem iye àwọn olùgbé ibẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́kanlélẹ́gbẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n ènìyàn 25000 orílẹ̀-èdè náà ibẹ́ ni wọ́n fẹnu kò sí wípé wọ́n ti bí...
johanu onitebomi oníwàásùjòhánù onitebomi jẹ́ oníwàásù ní agbègbè odò jọ́dánì ní àkókò tirè
frank santopadre frank santopadre february 7 1961 jẹ́ ònkọ̀wé ará amẹ́ríkà
àìsùn kérésìmesì àìsùn kérésìmesì ni ọjọ́ tàbí ìrólé tí ó kàn kí ó tó kan ọjọ́ kérésìmesì ìjọ tí a fi ń ṣe ayẹyẹ ibí jésù ìjọ kérésìmesì jẹ́ ọjọ́ tí àwọn ènìyàn yẹ́ sí káàkiri àgbáyé àìsùn kérésìmesì sì wà lára àwọn ọjọ́ tí wón yẹ́ sí ní ìrètí ọjọ́ kérésìmesì wọ́n ma ń ka ọjọ́ méjèèjì gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ ayẹyẹ tí ó ṣe pàtàk...
ọmọlẹ́yìn ní kristẹni ní àwùjọ kristẹni ọmọlẹ́yìn ni àwọn tí ó ti pinu láti tẹ̀lẹ́ jesu wọ́n lo ọ̀rọ̀ yìí ní majẹmu titun nínú àwọn ìwé ìhìn rere àti ìwé ìṣe àwọn àpọ́sítélì ní ayé àtijó ọmọlẹ́yìn jẹ́ ẹni tí ó ti pinu láti tẹ̀lé olùkọ́ rẹ̀ ọmọlẹ́yìn yàtò sí akẹ́kọ̀ọ́ ọmọlẹ́yìn nínú bíbélì jẹ́ ẹni tí ó ń ṣe àfarawé ayé ...
ìbí jesu àwọn ìwé ihinrere lúùkù àti mátíù ṣàpèjúwe ìbí jesu àwọn ẹ̀rí méjèèjì gbà wípé a bí jesu kristi ní bethlehemu judea àti pé ìyá rẹ̀ ní afesona kan jósẹ́fù ẹni tí ó wá láti ìran davidi ọba tí ko sì ń ṣe bàbá jesu ìtàn ibí jesu ni àwọn kristẹni fi ṣe isiro ọjọ́ ayẹyẹ kérésìmesì
davidi oba davidi gẹ́gẹ́ bí bíbélì ti sọ ni ọba kẹta ìjọba àpapò isreali awon ìwé sámúẹ́lì sọ nipa ti davidi pé ó jẹ́ ó domo kùnrin olùsọ́ agutan ẹni tí ó gbajugbaja lẹ́yìn ìgbà tí ó pa goliati jagunjagun alágbára ará filisteni ní is gúúsù àti canani èyí mú kí saalu féràn davidi davidi sì tún di ọ̀rẹ́ jónátánì ọmọ saal...
goliati goliati jé òmìrán kan tí bíbélì sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ nínú ìwé sámúẹ́lì bíbélì ṣàpèjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi òmìrán ara filistini kan tí davidi ségun lójú ogun
datro fofana french footballer david datro fofana wọ́n bí i lọ́jọ́ 22 oṣù kejìlá ọdún 2002 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ṣiṣẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè ivory coast tí ó ń gbá bọ́ọ̀lù fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ṣiṣẹ́ chelsea lórílẹ̀-èdè england bẹ́ẹ̀ náà ló ń gbá bọ́ọ̀lù fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù tí orílẹ̀-èdè ivory coast iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí a...
kuopio kuopio jẹ ilu inu ilẹ ni fínlándì o wa ni ibuso 390 ni ariwa ti helsinki olu-ilu naa o fẹrẹ to eniyan 120000 ngbe ni kuopio
aalo oòrùn àti osupa ààlọ́ òòrùn ati òṣùpá ààlọ́ mi dá lórí òòrùn àti osupa ààlọ́ oooooo ààlọ ní ìgbà ìwásẹ̀ ọba òde ọ̀run ní nṣe alákoso ohun gbogbo ìkáwọ́ rẹ̀ ṣì ni gbogbo ohun tí a dá wà ọba ọdẹ ọ̀run ní ìyàwó ósì tún bí ọmọ méjì òòrùn àti òṣùpá ni ọmọ méjì tí ọba òde ọ̀run bí òrùn àti òsùpá fẹ́ràn ara wọn gidigidi ...
aalo ilé àti olorun àalọ́ yìí dá lórí ilẹ̀ àti ọlọ́run ààlọ́ oooo ààlọ́ ní ayé àtijó ọ̀rẹ́ ni ilẹ̀ àti ọlọ́run bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ibùgbé wọn jìnà sí ara wọn àwọn méjèèjì a máa wá ara wọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni ọlọ́run máa ń sọ̀kalẹ̀ láti wá bá ilẹ̀ ṣeré ní ọjọ́ kan àwọn méjèèjì pinnu láti dẹ̀'gbẹ́ lọ kí àwon lè pa ẹran wọ́n...
aalo ìjàpá àti àná re ìjàpá àti àna rẹ̀ àlọ́ ooo àlọ́ ọọọ àlọ́ yìí dá lórí ìjàpá àti àna rẹ gbogbo wa ni a ti mọ ìjàpátìrókò ọkọ yánníbo gẹ́gẹ́ bíi ọlọ́gbọ́nẹ̀wẹ́ àti ọ̀kánjúà tí ó sì tún jẹ́ tìfunlọ̀ràn ní ọjọ́ kan ìjàpá gba ilé àna rẹ̀ lọ láti lọ kí wọn nígbà tí ó dé ilé àna rẹ̀ wọ́n ṣe àpọ́nlé rẹ̀ dáadáa ṣùgbọ́n bí ...
aalo obìnrin alaigboran ọmọbìnrin aláìgbọràn ààlọ́ ooooo àalọ̀ àlọ́ yí dá fìrìgbagbo ó dá lórí ọmọbìnrin aláìgbọràn kan ni ayé àtijóọmọbìnrin kan wà ní ìlú kan ọmọbìnrin yìí rẹwà bí egbin gbogbo àwọn ọmọkùnrin ni ó fé fi s'aya ṣùgbọ́n kò gbà fún ẹnì kankan nínú wọn àwọn òbí rẹ ni yan ọkọ fún ṣùgbọ́n kò tẹ́lẹ̀ ẹniti wọn...
aalo obìnrin kan àti ọmọ rẹ meta ààlọ́ obìnrin kan àti àwọn ọmọ rẹ̀ mẹ́ta ààlọ́ oooo ààlọ́ àalọ́ yí dá fìrìgbagbo ó dá lórí obìnrin kan àti àwọn ọmọ rẹ̀ mẹ́ta ni ìlú kan orúkọ ìlú náà ni olówó obìnrin kan wà tí ó bí ọmọ mẹ́ta orúkọ àwọn ọmọ náà ni wẹ́rẹ́wẹ́rẹ́ laá ṣẹ́gi àràwàrà làá wọ̀gbẹ́ àti ọmọniyùn tí ó jẹ́ àbígbẹ̀...
aalo ìrókò àti olúróhunbí olúróhunbí àti iroko àlọ́ oo àlọ́ ọọ àlọ́ yìí dá lórí olurohunbi àti olúwéré ní ayé àtijó obìnrin kan wà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ olúróhunbí obìnrin yìí kò sì fi inú soyún bẹ́ẹ̀ ni kò fẹ̀yin gbọ́mọ pọ̀n èyí jásí pé ó yàgàn ó wá ọmọ títí ṣùgbọ́n pàbó ló ń já sí dípò kí ó dúró de iṣẹ́ olódùmarè ó gba ...
àṣà ìkíni ní àwùjọ yorùbá gbajúgbajà àṣà yorùbá ìkíni jẹ́ ní àwùjọ yorùbá ó jẹ́ àṣà àwọn ènìyàn àwùjọ náà láti máa kí ara wọn ní gbogbo àwọn àkókò tí wọ́n bá bá ara wọn yorùbá gbàgbọ́ pé ìkínni jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọ̀nà tí ènìyàn lè gbà láti fi ọmọlúàbí rẹ̀ hàn ní àwùjọ yorùbá bí ọmọ bá jí ní àárọ̀ irú ọmọ bẹ́ẹ̀ gbọdọ̀ ...
2023 <ns>10</ns> <id>10717</id> <revision> <id>160243</id> <parentid>157824</parentid> <timestamp>2011-01-04t164512z</timestamp> <contributor> <username>demmy</username> <id>193</id> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> ọ̀rúndún | ọ̀rúndún 210k ◄◄ | | | 2023 ọdún tí a wà lọ́wọ́ nínú kàlẹ́...
2023 ní nàìjíríà àtòjọ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ 2023 ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà
arnold
kola adewusi nigerian politiciankola adewusi jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ẹni tí ó jẹ́ ìgbàkejì gómìnà ìpínlè osun láti oṣù kọkànlá ọdún 2022 wọ́n diboyan adewusi gẹ́gẹ́ bi ìgbàkejì gomina ìpínlè osun nínú ìdìbọ̀ yan gómìnà ìpínlè osun tí ó wáyé ní ọdun 2022
eagle ẹyẹ àṣá ẹyẹ àṣá jẹ́ ẹyẹ tí ó ma ń pa àwọn ẹranko kékèké tàbí ẹja inú omi jẹ gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ àṣá jẹ́ ìkan ninú ìran àwọn ẹyẹ tí àwọn gẹ̀ẹ́sì ń pe ní accipitridae ẹ̀yà àwọn ìran ẹyẹ yí tó 68 tí wọ́npọ̀ sí àwọn agbègbè bíi eurasia and africa yàtọ̀ sí àwọn agbègbè tí a mẹ́nubà yí ẹ̀ya mẹ́rìnlá outside ọ̀tọ̀ ni ó tún ...
fish oil òróró ẹja oil derived from the tissues of oily fish boilerplate seealso>ẹ tún wo omega-3 acid ethyl esters òróró ẹja jẹ́ ìran òróró kan tí wọ́n ma ń rí láti ara àwọn ẹja tí wọ́n lọ́ràá òróró ẹja yí ma ń ní àwọn èròjà aṣaralóore flomega-3 tí ó ma ma ń fún ara ní ọ̀rá tí ó péye lára àwọn aṣaralóore yí ni eicosap...
lionel messi lionel andrés messi tí a tún mọ̀ sí leo messi jẹ́ ògbólógbòó agbaboolu ọmọ orílè-èdè argentina tí ó ń gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ agbaboolu paris saint-germain messi gba ifì èye ballon d'or gégé bi agbábóólù tí ó dára jùlo ní gbogbo àgbáyé fún ìgbà keje ní odún 2021 eléyí mu fi méjì ju ti cristiano ronaldo ti o ...
òróró viscous water-insoluble liquid òróró jẹ́ ohun èlò kan tí ó gbajúmọ̀ tí wọ́n jẹ́ kẹ́míkà tí wọ́n ṣe láti ara hydrocarbons tí ó sì tún jẹ́ ́̀hydrophobic tí wọn kò fi omi sínú rẹ̀ rárá òróró sábà ma ń jẹ́ ohun tí ó lè gbaná látàrí surface active tí ó wà nínú rẹ̀ oríṣi òróró tí ó wà òróró ohun abẹmí òróró ohun abẹmí ...