raw_text
stringlengths
2
128k
yunifásitì adekunle ajasin yunifásitì adekunle ajasin akungba-akoko aaua jẹ́ ọ̀kan lára àwọn yunifásitì ìjọba ìpínlè ondo yunifásitì náà wà ní akungba akoko ìpínlẹ̀ òndó nàìjíríà ìtàn ìjọba ìpínlè ondo kókó dá yunifásitì adekunle ajasin kalè gẹ́gẹ́ bi yunifásítì obafemi awolowo ní ọdún 1982 adarí yunifásitì náà nígbà y...
mọ́tò mobile machine that transports people animals or cargo ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa the means of transportation fún ìtumọ́ míràn ẹ wo mọ́tò ìṣojútùú ọkọ̀ tàbí mọ́tò ni ó wá láti inú èdè ni ó jẹ́ ẹ̀rọ tí ó ń gbé ènìyàn tàbí ẹrù láti ibìkan sí ibòmíràn ọkọ̀ lè jẹ́ kẹ̀kẹ́ alùpùpù kẹ̀kẹ́ ọkọ̀ àjàgbé rélùwéè ọkọ̀ ojú-omi ọk...
rélùwéè rélùwéè tí a tún mọ̀ sí ọkọ̀ ojú-irin jẹ́ ọ̀nà kan pàtakì tí ọmọnìyàn ṣàgbékalẹ̀ rẹ̀ láti fi ma ṣèrìnàjò láti ibì kan sí òmíràn ìyàtọ̀ rélùwéè sí ọkọ̀ ajúpópó ni wípé kìí rìn lójú títì tí a tẹ́ pẹrẹsẹ àyà fi ojú irin tí a ti tó kalẹ̀ láti ibìkán sí ibòmíràn àwọn irin tí wọ́n tó kalẹ̀ kí ọkọ̀ ojú-irirn yí ń gbà ...
ẹran meat from cattle ẹran jẹ́ orúkọ gbogbo gbò fún ẹran tí a lè rí lára ara ẹran yálà ti ewúrẹ́ tàbí ti màlúù nígbà láé láé àwọn ọmọ ènìyàn ma ń dẹdẹ àwọn ẹranko láti pa wọ́n fún jíjẹ amọ̀ nígbà tí ó yá wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí ń rè tàbí sìn wọ́n gẹ́gẹ́ bí ohun ọ̀sìn ní ilé tí wọ́n sì ma ń mú wọn pajẹ nígbà tí àyè rẹ̀ bá ṣì síl...
adìyẹ adìyẹ gallus gallus domesticus jẹ́ ẹ̀yà ẹyẹ àti ẹranko ilé tí a ń sìn ní ilé tí wọ́n sì pín sí ẹ̀yà oríṣiríṣi bíi grey and the ceylon junglefowl tí a lè rí ní apá southeastern asia a lè akọ adìyẹ ní akọ tàbí kí a pèé ní àkùkọ yálà èyí tí ó ti dàgbà tàbí èyí ó ṣẹ̀sẹ̀ ń dàgbà bọ̀ èyí tí ó jẹ́ abo ni a lè pe ní abo ...
ẹyin organic vessel in which an embryo first begins to develop ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa biological eggs fún eggs as food ẹ wo ẹyin gẹ́gẹ́ bí óúnjẹ fún other uses ẹ wo egg disambiguation ẹyin ni a lè pe ní àpò-lùkẹ́ tomi-jẹ̀jẹ̀ tí ó dara pọ̀ mọ́ra wọn tí ó ń di òròmọdìyẹ nígbà tí ó bá ti tó àsìkò rẹ̀ púpọ̀ awọn kòkòrò tí ...
àyìnlá fíìmù àgbéléwò àyìnlá jẹ́ fíìmù àgbéléwò olókìkí ajẹmórin kan tí ó dá lórí ìtàn ìgbésí aye àyìnlá yusuf tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí àyìnlá ọmọwúrà olórin àpàlà tí máníjà rẹ̀ tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ báyéwù gún pa nínú ìjà ilé ọtí ní ọjọ́ 6 oṣù èbìbí ọdún 1980 ní ìlú abẹ́òkúta fíìmù náà jẹ́ ṣíṣàfihàn ní ọjọ́ 13 oṣù okúdù ọ...
eré ìdárayá forms of competitive activity usually physical eré ìdárayá ni a lè pe ní ìfigagbága tí a ń fi gbogbo ara ṣe yálà níbi eré ni tàbí ìdíje tí a fi ń mú àláfíà ara le koko tàbí kí á lòó láti fi nímọ̀ nípa irúfẹ́ eré ìdárayá bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ òjòọ́ ẹni tí a sì tún fi ń ṣe ohun ìgbádùn fún àwọn ònwòran eré ìdá...
sport
janet febisola adeyemi janet febisola adeyemi ọjọ́ ìbí jẹ́ oṣù kẹjọ ọdún 1958 jẹ́ ààrẹ tí ó wà ní pò leke fún àwọn obìnrin tí wọn ń ṣiṣẹ́ mining ní orílé èdè nàìjíríà àti alàfaramọ́ fún àwọn oníṣe mining ní ilé ókéré o ṣiṣẹ́ lábẹ́ àwọn ìgbìmò fún gómìnà tí wọn yàn ní ìpínlè ondó tí wọn pè ní strategic development and p...
àyìnlá fíìmù àgbéléw
mr macaroni adebowale debo adedayo tí a bí ní ọjọ́ kẹta oṣù karùn-ún ọdún 1993 tí orúkọ ìnagijẹ́ rè jẹ́ mr macaroni jẹ́ òṣèré orílè-èdè nàìjíríà apanilérìn-ín afèròhàn-lórí-èrọ-ayéllujára àti ajà-fẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn ó kọ́ bí a ṣe ń pani lérìn-ín ó sì di gbajúmọ̀ látàrí àwọn fọ́nrán kékèèké rẹ̀ tó ti máa ń fi ara rẹ̀ hàn ...
james febisola adeyemi
àtòjọ àwọn fíìmù nàìjíríà ti ọdún 2023 èyí ni àtòjọ àwọn fíìmù nàìjíríà ti wọ́n ṣe jáde ní ọdun 2023
ade laoye ade laoye jẹ́ òṣèrébìnrin láti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní pennsylvania state university níbi tí ó ti kọ́ nípa eré orí-ìtàgé ade laoye kọ́kọ́ hàn sí gbàgede nínú fíìmù àgbéléwò knocking on heaven's door láti ọwọ́ emem isong ade tún hàn nínú lunchtime heroes láti ọwọ́ seyi babatope àti nínú fíìmù k...
ìmọ̀ aáyan ògbufọ̀ study of translation as an academic disciplineìmọ̀ aáyan-ògbufọ̀ jẹ́ ìmọ̀ iṣẹ́ alákadá tí ó kó ọ̀pọ̀ ọ̀wọ́ pọ̀ tí ó sì ń dojú kọ lílo ètò tíọ́rì àpèjúwe àti ìṣàmúlò ìgbufọ̀ ṣíṣe tapítà àti ìsọdonílé gẹ́gẹ́ bí ẹ̀ka ìmọ̀ ọlọ́pọ̀ ẹ̀ka aáyan-ògbufọ̀ ṣe ọ̀pọ̀ ìmọ̀ láti inú àwọn ẹ̀ka-ẹ̀kọ tí wọ́n ṣe ìrànwọ...
translation studies
idanre
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ile oluji/okeigbo
nursultan
james febisola adeyemi
national hospital abuja national hospital abuja jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé ìwòsàn ní abuja fct nàìjíríà a dá ilé ìwòsàn náà kalẹ̀ lábé ètò family support programme initiative abdulsalami abubaka ni ẹni tí ó ṣẹ ìsílé ilé ìwòsàn náà ní 22 may 1999 orúkọ tí wọ́n kọ́kọ́ fún ilé ìwòsàn náà ni national hospital for women and ch...
federal university of technology
kylian mbappé french footballer born 1998 kylian mbappé lottin ti a bi 20 oṣu kejila ọdun 1998 jẹ agbabọọlu fun faranse kan ti o n gba iwaju fun egbe ligue 1 paris saint-germain ati ẹgbẹ orilẹ-ede france a kà si ọkan ninu awọn agbaboolu ti o dara julọ ni agbaye o jẹ olokiki fun awọn ege ti o ma n ge ati iyara gbe boolu...
titanic rms titanic jẹ́ ọkọ ojú omi ńlá kan tí ó rì sí òkun north atlantic ní ọjọ́ keedogun oṣù kẹrin15 april ọdún 1912 lẹ́yìn ìgbà tí ó kọlu òkúta omi dídì kan nígbà tí ó rìn ìrìn àjò láti southampton england sí new york city orílẹ̀ èdè america lára àwọn arin ìrìn àjò 2224 tí ó wà nínú ọkọ̀ náà ó lé ní 1500 sọ ẹ̀mí wọ...
buchi onyebuchi ojieh tí àwọn ènìyàn mọ̀ mọ́ orúkọ orí-ìtàgé rẹ̀ buchi wọ́n bí i ní april 4 1979 jẹ́ apanilẹ́rìn-ín nàìjíríà a-kọ-orin-sílẹ̀ òǹkọ̀wé àti òṣèré láti ìpínlè delta nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ìgbé-ayé àti ẹ̀kọ́ a bí buchi ní kwale ndokwa west ìpínlẹ̀ delta nàìjíríà ó lọ dsc nursery and primary school àti ovwian secon...
mc lively òṣẹ̀fẹ̀ orílé èdè nàìjíríà àti òṣèré michael sani amanesi tí ìnagige rẹ̀ jẹ́ mc lively jẹ̀ òṣèré àti òṣèfẹ̀ kàn ní orílé èdè nàìjíríà tí wọ́n bí ní ọjọ́ kefàdínlogun oṣù kẹjọ ọdún 1992 tí o jẹ́ ọmọ agenebode ní ìpìnlẹ̀ ẹdó ní orílè èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀ ìgbé ayé àti ètò ẹ̀kọ́ woọ́n bí mc lively sí ìpínlẹ̀ ọ...
basketmouth bright okpocha tí a bí ni ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹ́sàn-án ọdún 1978 ní ìpínlẹ̀ èkó tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ basketmouth tí gbogbo ènìyàn mò sí jẹ́ apanilẹ́rìín àti òṣèré ọmọ nàìjíríà ó ti ṣètò àwọn eré orin àwàdà ìmurasílẹ̀ olókìkí bíi basketmouth uncensored káàkiri àgbáyé basketmouth ti gbàlejò ìpeníjà àwàdà kan lórí...
immanuẹlla
henry fajemirokun henry oloyede fajemirokun con jẹ́ ògbóǹtarigì oníṣòwò orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n bí i ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kéje ọdún 1926 ó sì kú ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kejì ọdún 1978 òun pẹ̀lú adebayo adedeji ní ìgbàgbọ́ nínú ètò-ọrọ̀-ajẹ́ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè ti ìwọ̀-oòrùn áfíríkà èyí tí ó di ohun tí à ń pè ...
henrry fajemirokun
afeez oyétòrò
bọ́lájí amúṣàn-án
quinton aaron quinton aaron tí a bí ní ọjọ́ karùn-úndínlógún oṣù kẹjọ ọdún 1984 jẹ́ òṣèré orílẹ̀-èdè american actor ó ṣe fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀ nínú eré michel gondry tó ń jẹ́ be kind rewind ẹ̀dá-ìtàn tó kọ́kọ́ ṣe ni ibi tí ó ti ṣe michael oher nínú fíìmù kan ní ọdún 2009 tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́the blind side ìbèrẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé r...
wole oladiyun wole oladiyun tí ọjọ́ ìbí jẹ́ ọjọ́ kejì oṣù kẹrin ọdún 1959 jẹ́ àlùfáà kàn ní orílé èdè nàìjíríà òǹkọ̀wẹ̀ onísòwò ìmọ ẹ̀rọ engineer àti olùdarí/olùdásílẹ̀ ilé ìjósìn tí orúko rè ń jẹ́ christ of living spring apostolic ministry clam ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé ayé àti ètò ẹ̀kọ́ àlùfáà oladiyun jẹ́ ọmọ bíbí ilé olúj...
ira aldridge ira frederick aldridge tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù keje ọdún 1807 tí ó sì di olóògbé ní ọjọ́ keje oṣù kejọ ọdún1867 jẹ́ òṣèrékùnrin àti adarí eré orí-ìtàgé tó wá láti orílẹ̀-èdè american ó di ìlú-mọ̀ọ́-ká látàrí fífi ẹ̀dá-ìtàn shakespeate hàn james hewlett àti aldridge ni a lè pè ní àwọn aláwọ̀-dúdú à...
flex alexander mark alexander knox tí a bí ní ọjọ́ karùndínlógún oṣù kẹrin ọdún 1970 tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí flex alexander tàbí flex jẹ́ òṣèrékùnrin apanilẹ́rì-ín àti oníjó láti orílẹ̀-èdè amerika ó bẹ̀ẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ lórí ẹ̀rọ amóhùn-máwòrán ní ọdún 2001 sí ọdún 2006 alexander tún gbé ẹ̀dá-ìtàn oríṣiríṣi wọ̀ nínú àw...
khandi alexander harriet rene khandi alexander tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹsàn-án ọdún 1957 jẹ́ oníjọ́ akọ́nimọ̀ọ́jó àti òṣèré orílẹ̀-èdè american ó bẹ̀ẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi oníjó ní ọdún 1980s ó sì bèẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ akọ́nimọ̀ọ́jó fún whitney houston láti ọdún 1988 wọ 1992
mark angel aláwadà mark angel tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 1991 jẹ́ ọ̀kan lára àwọn gbajúmọ̀ aláwàdà ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ fún àwọn eré àwàdà mark angel comedy series ní orí ìkànnì youtube èyí tí òun àti àwọn ará ilé rẹ̀ bi emmanuella samuel àti aunty success madubuike ìkànnì mark a...
taaooma maryam apaokagi tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí taaooma jẹ́ apanilẹ́rìn-ín orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó tún jẹ́ ayàwòrán lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí òun ni olùdarí àti olùdásílẹ̀ chop tao èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ oúnjẹ ó sì ń darí ilé-iṣẹ́ greenade ó di gbajúgbajà látàrí àwo eré apanilẹ́rì-ín rẹ̀ lórí ẹ̀rọ ayárabíàṣá ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ a ...
kenny blaq otolorin kehinde peter tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ kenny blaq jẹ́ olórin àti apanilẹ́rìn-ín orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó ṣeré níbi ayẹyẹ kejì ti naija independence àti ayẹyẹ àṣekágbá ti africa magic ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ kenny blaq kàwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní ejigbo ní ìpínlẹ̀ èkó ó ní láti kúrò ní ss3 láti lọ...
ajiona alexus american actressajiona alexus brown tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹta ọdún 1996 jẹ́ òṣèrébìrin orílẹ̀ èdè america tó di ìlúmọ̀ọ́ká látàrí ìfarahàn rè nínú eré the rickey smiley empire 13 reasons why acrimony and breaking in ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ yìí ní ọdún 2008 nígbà tó pé ọmọdún méjìlá ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ...
sam loco efe sam loco efe tí a bí ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1945 tó sì di olóògbé ní ọjọ́ keje oṣù keje ọdún 2011 tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ sam loco efeeimwonkiyeke tí wọ́n bí ní ìpínlẹ̀ ẹnúgu jẹ́ òṣèrékùnrin àti olùdarí eré ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí efe sí ìpínlẹ̀ ẹnúgu ó jẹ́ ọmọ arase ...
noni madueke english footballer chukwunonso noni tristan madueke wọ́n bí i lọ́jọ́ kẹwàá oṣù kẹta ọdún 2002 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ṣiṣẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè england tí ó ń gbá bọ́ọ̀lù fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ṣiṣẹ́ psv
duncan mighty duncan wene mighty okechukwu wọ́n bíi ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1983 ẹni tí a mọ̀ sí duncan mighty jẹ́ olórin orílẹ̀ èdè nàìjíríà akọrin àti olóòótú orin láti ìlú obio-akpor ní ìpínlẹ̀ rivers bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé irú ọ̀wọ́ orin rẹ̀ wà lábẹ́ ọ̀wọ́ orin ìdárayá tí àwọn olóyìnbó pè ní high-level t...
fífún ọmọ lọ́yàn fífún ọmọ lọ́yàn tàbí fífún ọmọ lọmú túmọ̀ sí fífún ọmọdẹ́ tàbí ọmọ jòjòló ní omi ọ̀yàn gẹ́gẹ́ bíi oúnjẹ o le jẹ́ fífún ọmọ ní omi oyàn láti inu oyàn tàbí fífún ọmọ ní omi oyàn tí a ti fi owó fún jáde láti inú oyàn àjọ world health organization who pa á ní arowà pé kí ìfún ọmọ lọ́yàn bẹ̀rẹ̀ láàrin wákà...
viola davis viola davis tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹjọ ọdún 1965 jẹ́ òṣèrébìnrin ilẹ̀ amerika ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ bíi academy award primetime emmy award àti àmì-ẹ̀yẹtony méjì ó sì tún jẹ́ ọmọ african american tó gba triple crown of acting ìwé ìròyìn times ṣe àfihàn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi ọ̀kan lára àwọn ọgọ́rùn-ún o...
mahershala ali mahershala ali tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ mahershalalhashbaz gilmore tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kejì ọdún 1974 jẹ́ òṣèrékùnrin láti orílẹ̀-èdè amerika ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ bíi academy awards méjì golden globe award àti primetime emmy award ìwé ìròyìn times to orúkọ rẹ̀ pọ̀ mó àwọn ọgọ́rùn...
ataare ataare jẹ́ ata ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èròjà fún ṣíṣe ọbè ní ilẹ̀-adúláwọ̀ó sì wúlò fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan bíi iṣẹ́ àmúṣagbára àti fífi ṣe ìwúre láwùjọ yorùbá
troian bellisario troian avery bellisario a bí i ní ọjọ́ 28 oṣù ọ̀wàrà ọdún 1985 jẹ́ òṣèrébìnrin orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga university of southern california ní ọdún 2010 ó gba ipò tí ó fún un ní ọ̀nà àbáyọ gẹ́gẹ́ bi spencer hastings nínú eré ìtàgé atòtẹ̀léra freeform tí orúkọ eré náà ń...
james baskett james franklin baskett ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kejì ọdún 1904 ọjọ́ kẹsàn-án oṣù keje ọdún 1948 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà òṣèré oní tíátà àti olórin ni pẹ̀lú ó kópa nínú eré song of the south tí disney ṣe àgbéjáde rẹ̀ ní ọdún 1946 gẹ́gẹ́ bíi ọńkúú remus tó kọ orin zip-a-dee-doo-dah fún ìdánimọ̀ lórí ipa t...
philip bailey philip bailey jẹ́ ọmọ ọkùnrin kan pàtó èyí tí a bí ni ọjọ́ kẹjọ oṣù kàrún-un ọdún 1951 in ilẹ̀ amẹ́ríkào jẹ rb o máa n ko orin ti ẹ̀mí o jẹ olórin tí ó sí tún máa nkọ orin sílẹ̀ ti a sì tún mọ sí tún mọ sí ẹni tí o máa n síwájú orin ni kikọ lati inu ohun ẹnupelu àwọn ọmọ group founder maurice white ti ayé...
louise beavers louise beavers march 8 1902 october 26 1962 jẹ́ òṣèrébìnrin fíìmù agbéléwò àti tẹlifíṣọ́ọ̀nù ní orílẹ̀ èdè amerika láti ọdún 1920 sí ọdún 1960 ó kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù àti ètò orí tẹlifíṣọ́ọ̀nù méjì tó gbajúmọ̀ jù lọ ẹrú tàbí ọmọ-ọ̀dọ̀ ni wọ́n sábà máa ń lò ó fún nínú àwọn eré náà
eva marcille eva marcille sterling tí orúkọ bàbá rẹ̀ jẹ́ pigford tí a bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1984 jẹ́ òṣèrébìnrin ti ilẹ̀ amerika oníṣé-oge àti gbajúgbajà lórí ẹ̀rọ amóhùn-máwòrán ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ nígbà tó jáwé olúborí nínú ìdíje ẹlẹ́ẹ̀kẹta ti america's next top model ìbẹ̀rẹ̀pèpẹ̀ ayé rẹ̀ a bí arábìnrin ster...
josh2funny chibuike josh alfred tí gbogbo ayé mọ̀ sí josh2funny jẹ́ adẹ́rìn-ín-pòṣónú òsèré àti olórin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbésí ayé rẹ̀ a bí josh2funny ní ìpínlẹ̀ anámbra ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kejìlá ọdún 1990
jennifer beals jennifer beals tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kejìlá ọdún 1963 jẹ́ òṣèrébìnrin ará amerika àti àwòkọ́ṣe ọ̀dọ́mọkùnrin télẹ̀ ó ṣe ìfarahàn àkọ́kọ́ nínú my bodyguards ní ọdún 1980 kí ó tó gba ìyin pàtàkì fún ipa rẹ̀ nínú flashdance ní ọdún 1983 èyí sì mu gba àmì-ẹ̀yẹ naacp fún òṣèré tíátà tó tayọ jù lọ ...
avery brooks avery franklin brooks tí wọn bí october 2 1948 jẹ́ òṣeré amẹ́ríkà olùdarí akọrin aroso àti akọ̀wé ó jẹ́ gbajúmọ̀ fún àwọn ère orí-ìtàgé bí captain benjamin sisko lórí star trek deep space nine bí hawk nínú spenser for hire àti its spinoff a man called hawk àti bí dókítà bob sweeney nínú the academy awardti...
ọba fakayode faluade ọba fakayode faluade jẹ́ olú ti ibogun èyí tí ó wà ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ifọ̀
michael beach michael anthony beach tí wọ́n bi ní oṣù kẹwàá ọgbọ́n ọjọ́ ní 1963ọ́ jẹ́ òsẹ̀rẹ́ ti ilẹ̀ amẹ́ríkà tí ó kópa nínú eré lean on me1989 one false move 1992 short cuts 1993 waiting to exhale 1995 a family thing 1996 soul food 1997 àti eré aquaman 2018 lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán ó ṣerẹ́ al boulet lórí nbc eré oníṣè...
dres the rapper andres dres vargas-titus ọjọ́ ìbí jẹ́ oṣù kẹta ọjọ́ kejidinlogun ọdún 1967 jẹ́ òṣeré hip hop ni orile ede amerika ó jẹ́ olori fún àwọn òṣeré tí orúkọ ègbé wọn jẹ́ alternate hip hop duo black sheep group kí ó tó dá dúró ìṣe dres dá egbe black sheep kalẹ ni 1989 pẹ̀lú mista lawnge àwọn mejeeji kọ́kọ́ ṣeré...
glynn turman glynn russell turman tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kìíní ọdún 1947 jẹ́ òṣèré ilẹ̀ amẹ́ríkà ó sì tún jẹ́ ònkọ̀wé ayẹ̀wéwò olùdarí àti agbátẹrù ètò orí tẹlifíṣọ́ọ̀nù ibẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí turman sí ìlú new york ìwádìí fi yé wa pé ó tan mọ́ àwọn ará edo ní orílẹ̀-èdè naijiria turman kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní high scho...
avery brooks
louise beavers
moin moin mọ́ín-mọ́ín ọ̀lẹ̀lẹ̀ tàbí ọ̀ọ̀lẹ̀ jẹ́ ẹ̀wà tí a bo èpo rẹ̀ tí a lọ̀ tí a sì fi àwọn èròjà bíi ata epo iyọ̀ edé iyọ̀ àti àwọn èròjà míràn sí ṣáájú kí wọ́n tó sè é lórí iná lọ́pọ̀ ìgbà wọ́n ma ń fi àlùbọ́sà atalẹ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ kun kí ó lè dùn un jẹ móí-mọ́í jẹ́ óunjẹ ìbílẹ̀ yorùbá tí wọ́n wà ní apá ìwọ̀ ì...
joy bryant joy bryant gẹ́gẹ́ bí i orúkọ rẹ̀ jẹ́ òṣèrébìnrin oníṣòwò àti oníṣẹ́-oge ọmọ ilẹ̀ amẹ́ríkà ó ti kópa tàbí farahàn nínú-un ogunlọ́gọ̀ eré àti iṣẹ́ẹ móhùn-máwòrán láti ìgbà tó ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ẹ rẹ̀ ní ọdún 2001 a bí i ní ọjọ́kejìdínlógún osù kẹwàá ọdún-un 1974 sí bronx ìpínlẹ̀ new york arúgbóbìnrin òbí i rẹ̀ ló t...
keith richards keith richards kiθ ˈɹɪt͡ʃədz 1 ti a bi ni oṣu kejila ọjọ 18 ọdun 1943 ni dartford kent england jẹ akọrin ara ilu gẹẹsi akọrin onigita oludasile ni ọdun 1962 pẹlu mick jagger brian jones ati ian stewart ti ẹgbẹ apata the sẹsẹ okuta paapọ pẹlu mick jagger ni ajọṣepọ kan ti wọn pe ni awọn twins glimmer o kọ...
kiruki kiriku ti a bí ní oṣù kejìlá ojo kẹtàdínlógún ọdún 2014 tí orúkọ àbísọ rẹ sì jẹ enorense victory jẹ́ ọmọ nàìjíríà aláwàdà òǹkọ̀wẹ́ alátìnúdá àti ọmọdé òṣeré ayé rẹ̀ kiriku jẹ́ ọmọ benin láti edo state ó jẹ́ ará urhobo ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀ẹ̀rẹ̀ ni ó wà òun ni àbúrò umbrella boy tó tún jẹ́ alákòóso rẹ̀ òun ni ọmọ à...
àwọn ẹ̀gbá àwọn ẹ̀gbá jẹ́ ẹ̀ka ẹ̀yà yorùbá ní apá ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ nàìjíríà ọ̀pọ̀ nínú wọn ni wọn wá láti àárín ìpínlẹ̀ ògùn tí í ṣe ogun central senatorial district àpapọ̀ ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́fà ni ó parapọ̀ di ogun central senatorial district ni ìpínlẹ̀ ògùn àwọn wọ̀nyí ni agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá abẹ́òkúta agbègbè ìjọb...
èso ikoyi ẹ̀ṣọ́ ikòyí orílẹ̀ yorùbá kan ni èyí jẹ́ oríkì wọn ẹ̀ṣọ́ ò ríkúsá ọmọ a-lérí ikú pogun ọmọ agbọ̀n tíí béèrè ìjà
adérónkẹ́ adéolá
akinloyè akínyẹmí
ìró àti bùbá iró ati bùbá jẹ́ orúkọ aṣọ tí ó wọ́pọ̀ láàrín àwọn obìnrin ẹ̀yà yorùbá ní apá ìwọ̀ oòrùn orílẹ̀-èdè nàìjíríà má a ń wọ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ aṣọ yìí jẹ́ onípele márùn-ún lára rẹ ni ìró èyí tí ó tóbi jù lọ tí wọ́n máa ń ró mọ́ ìbàdí nígbà tí bùbá jẹ́ ẹ̀wù tí wọ́n ń máa ń wọ̀ lé orí ìró gèlè ní tirẹ̀ ni wọ́n máa ń wé ...
túndé ìdíàgbọn
túndé kèlání
joseph òkéfọláhàn ọdúnjọ
ẹ̀bùn olóyèdé ọlá-ìyá
àyìnlá ọmọwúrà
ẹ̀gbá aké egba ake tí a tún mọ̀ sí ẹ̀gbá aláké jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀ka márààrún tí ẹ̀gbá pín sí àwọn ẹ̀ka yòókù ni oke-ona gbagura owu àti ibara ìtàn fi yé wa pé ibara wà lára yewa kì í ṣe ẹ̀gbá àmọ́ agbègbè abẹ́òkúta ni ó wà báyìí aláké ti ìlú ẹ̀gbá ni ọba tàbí olórí gbogbo ẹ̀yà ẹ̀gbá àwọn olórí èyí ni àtòjọ àwọn oló...
aláké ti ìlú ẹ̀gbá aláké ti ìlú ẹ̀gbá ni orúkọ oyè ọba ti ìlú ẹ̀gbá èyí tó wà ní abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ ògùn ní apá ìwọ̀-oòrùn ilè nàìjíríà ẹ̀gbá pín sí ẹ̀gbá aké òwu oke-ona àti gbagura ìtàn sagbua okukenu di aláké ti ìlú ègbá tó kọ́kọ́ jẹ ó sì jọba láti ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹjọ ọdún 1854 wọ ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún...
ègbá aké
henry townsend missionary henry townsend tí a bí ní ọdún 1815 tí ó sì kú ní ọdún 1886 jẹ́ ajíǹhere ti ìjọ anglican ní orílè-èdè nàìjíríà wọ́n fi àmì-òróró yàn án ní ìlú england ní ọdún 1842 ọdún kan náà ni townsend lọ sí sierra leone lẹ́yìn tí ó ṣiṣẹ́ níbè fún oṣù díẹ̀ wọ́n gbe lọ sí ilẹ̀ yoruba iṣẹ́ rẹ̀ láti ọdún 1846...
agbon igi agbon cocos nucifera jẹ eya igi ọpẹ arecaceae ati eya cocos kan soso ti o ku ohun ti a n pe ni agbon le tọka si gbogbo igi agbon koro esotabi eso oruko yii wa lati oruko coco' eyi ti o je oruko aguda atijo ti o tumo si ori tabi agbari
olatunde farombi olatunde farombi jé ọ̀jọ̀gbọ́n ìmọ̀ biochemistry àti molecular toxicology ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ royal society of chemistry frsc uk àti nigerian academy of science ó sì tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ african academy of sciences at academy of toxicological sciences ó gboyè ọ̀mọ̀wé nínú ìmọ̀ biochemistry láti ilé ẹ̀kọ́ gíga...
super eagles egbé agbá bóólù àfésè gbá okùnrin ti orílè-èdè naijiria ni wón pe ni super eaglestí wón má n se asójú orílè-èdè naijiria nínú ìdíje bóólù àfésè gbá kakiri agbáyéti egbé nigeria football federation nff n se alákoso won
gbenga agboola olugbenga agboola oon tí a bí ní ọdún 1985 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ èdè kọ̀mpútà àti oníṣirò ńlá òun ni olùdarí àti ọ̀gá ilé-iṣẹ́ flutterwave ipinle eko ni a bí agboolansí ó kàwé gboyè mba ní ilé-ìwé mit sloan school of management kí ó tó dá ilé-iṣẹ́ flutterwave sílẹ̀ pẹ̀lú iyinoluwa...
egba gbagura egba gbagura jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìpísísọ̀rí márùn-ún tí ẹ̀gbá pín sí èka yòókù ni ẹ̀gbá aké oke-ona òwu àti ibaraìtàn fi yé wa pé apá yewa ni ibara wà lohnìí pé kì í ṣe ẹ̀gbá bí ó tilè jé pé ìlú abéòkuta náà ló wà ó jẹ́ ìlú ìbílẹ̀ tó pààlà pẹ̀lú ìlú mìíràn láti mú kí ìṣèjọba rẹ̀ gà si agura ti gbagura ni o...
taiwo taiwo taiye taye taiyewo jẹ́ orúkọ yoruba tí àwọn yorùbá má ń fún ọmọ tí ó bá kókó wáyé nínú àwọn ìbejì ó tún mò sí ìbejì tí ó kókó tọ́ ayé wò tàbí ẹni tí ó wá ṣáájú kehinde bí ó tilè jẹ́ wípé taiwo ní ìbejì tí ó kókó wáyé àwọn yorùbá gbàgbó pé taiwo ni àbúrò wón sì tún gbàgbọ́ pé kehinde rán taiwo wá sínú ayé yì...
kehinde kehinde omokehinde jẹ́ orúkọ yorùbá tí wọ́n ń fún ọmọ ìkejì nínú àwọn ìbejì tàbí ọmọ tí ó wá lẹ́yìn taiwo bí ó tilè jẹ́ wípé taiwo ni ọmọ tí ó kókó wáyé àwọn yorùbá gbàgbó pé kehinde ni ẹ̀gbọ́n ṣùgbọ́n ó rán taiwo wá sáyé láti wá tó ayé wò
portable olorin portable tí orúkọ àbíṣọ rẹ̀ ń jẹ́ habeeb okikiola tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìlá oṣù kẹta ọdún 1994 jẹ́ olórin ìgbàlódé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà
adalu ounje adalu jẹ ounje kan ti á màn pe ni asáró ni orilẹ-ede naijiria ti a hún fí agbado ati ẹwa sè o de gbajumo laarin awọn yoruba ati awọn igbo igbaradi a o se agbado ati ewa lọtọ ki a to da awon mejéjì pápọ a ó sí fi epo púpa alubosa ata ati iyọ si ko le ba dun a má n jé adalu pelú ogede ati eja sisun
ijẹrisi iwe-aṣẹ awakọ ni benin ijẹrisi iwe-aṣẹ awakọ ni benin nigbati oludije kan ba gba ni pato si awọn idanwo iwe-aṣẹ awakọ fẹ lati ni aṣẹ lati wakọ ọkọ lati awọn wakati ti o tẹle ikede ti awọn abajade ijẹrisi ti a fun ni iwe-ẹri yii le jẹ lilo nipasẹ ẹni ti oro kan titi iwe-aṣẹ awakọ yoo wa o wulo fun akoko kan ti m...
agbaboolu agbábọ́ọ̀lù jẹ́ eléré-ìdárayá tó ń gbá oríṣiríṣi bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá oríṣi bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ni association football american football canadian football australian rules football gaelic football rugby league àti rugby union ìṣirò tí wọ́n ṣe fi yé wa pé iye àwọn agbábọ́ọ̀lù ní àgbááyé á tó 250 million àti pé ọ̀p...
bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀
ẹsẹ̀ ẹsẹ̀ jẹ́ ẹ̀yà ara tó ń mára dúró tó sì wà fún gbígbé ara láti ibìkan lọ sí ibòmííràn lásìkò gbígbé ara láti ibìkan lọ ibòmìíràn ẹsè máa ń nà
esè
richard brooks american screenwriter film director and producer 19121992 richard brooks may 18 1912 march 11 1992 ó jẹ́ àkọ̀wé ẹ̀ro alagbátà ti american òlùdarí fiimunkòwé àti aṣagbejade fiimu wọ́n yan fún oscars mẹ́jò nìdí isẹ rẹ́rwọ́n mọ s r blackboard jungle 1955 cat on a hot tin roof 1958 elmer gantry 1960 for wh...
owu ẹ̀yà owu jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ yorùbá ní ìwọ̀-oòrùn áfíríkà ago-owu ní abeokuta ni ibi ti àwọn owu ti pọ̀jù sí káàkiri ile yoruba ni a sì ti máa ń rí àwọn owu àjọṣepọ̀ ìjọba ilẹ̀ yorùbá gbòòrò kọjá ilẹ̀ nàìjíríà dé orílẹ̀-èdè benin àti togo orísun àkọsílẹ̀ ìtàn àwọn owu kọ́kọ́ wáyé lẹ́yìn ìtẹ̀dó wọn ní ago-owu ní...
david crosby david van cortlandt crosby tí wón bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹjọ ọdún 1914 tí ó sì kú ní ọjọ́ kejìdínlógún ọdún 2023jẹ́ akọrin àti olórin ọmọ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ohun tí ó kọ́kọ́ sọ ọ́ di gbajúmọ̀ ni jíjẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ẹ the byrds crosby ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwọn àwo-orin adáṣe mẹ́jọ bótilẹ̀jẹ́pé lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan ni lákòók...
eyi to gbeyin ninu wa eni to gbeyin wa jẹ́ eré ìṣe -ìṣèré ti 2013 ti o dàgbàsókè nípasè naughty dog ati a tẹjade nipasẹ sony computer entertainment awọn oṣere n ṣakoso joel onijagidijagan kan ti o ni iṣẹ pẹlu didari ọmọbirin ọdọ kan ellie kọja kan ranse si-apocalyptic united states ikẹhin ti wa ti dun lati irisi eniyan...
michael jackson iyasọtọ michael jackson 19582009 jẹ́ olórin ara ilu amẹrika kan akọrin ati onijo ti a mọ si “ọba agbejade”