raw_text
stringlengths
2
128k
kim kardashian kimberly noel kardashian tí a bí ní oṣù kẹwàá 21 1980 jẹ́ àwùjọ ará ìlú amẹ́ríkà kan ìhùwàsí mídíà àti arábìnrin oníṣòwò ó kókó di gba-jú-gba-jà lórí ẹ̀rọ agbáwòrán s'áfẹ́fẹ́ gẹ́gẹ́ bíi onídìrí ti paris hilton ṣùgbọ́n gba ànfàní àkíyèsí lẹ́hìn tí àwọn ìbálòpọ̀ téépù kim kardashian superstar tí wọ́n yà ní...
chris hemsworth christopher hemsworth am ti a bi 11 august 1983 jẹ oṣere ilu australia ó di gbajugbaja ati olokiki látara sise ẹ̀dá itan kim hyde ninu ere agbeleewo tẹlifiṣọn orile ede australia home and away 2004 2007 ṣaaju ki o to bẹrẹ iṣẹ fiimu ni hollywood ninu agbaye cinematic marvel mcu hemsworth bẹrẹ ṣise ẹ̀dá i...
k viswanath kasinadhuni viswanath 19 february 1930 - 2 february 2023 jẹ́ olùdarí fiimu india kn onkọwe iboju ati oṣere ọkan ninu awọn auteurs nla julọ ti sinima telugu o gba idanimọ kariaye fun awọn iṣẹ rẹ ati pe o jẹ mimọ fun idapọ sinima ti o jọra pẹlu sinima akọkọ a bu ọla fun pẹlu “eye ti gbogbo eniyan” ni “ besanç...
susan wojcicki susan diane wojcicki tí a bí ní oṣu keje ọjọ́ 5 ọdún 1968 jẹ́ olùdarí ìdókòwò ara ìlú poland-amẹrika tí ó jẹ́ alákòóso youtube láti ọdún 2014 àkójọpọ̀ ọrọ̀ rẹ̀ jẹ́ 765 million ní ọdún 2022 wojcicki ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ ìmọọ-ẹ̀rọ fún ogún ọdún ó kópa nínú ìṣẹ̀dá google ní ọdún 1998 nígbà tí àwọn olùdásílẹ̀ r...
destiny's child destiny's child fígbá kan jẹ́ ẹgbẹ́ orin kan ni ilẹ́ america tí àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin méta kan dá sílẹ̀ àwọn obìnrin náà ni beyoncé knowles kelly rowland àti michelle williams ẹgbẹ́ náà bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ wọn gẹ́gẹ́ bíi olórin pẹ̀lú orúkọ girl's tyme tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 1990 ní houston texas lẹ́yìn ọdún díẹ̀...
sam smith samuel frederick smith tí a bí ní 19 may 1992 jẹ́ akọrin àti aṣẹ̀dá orin ọmọ orílè-èdè england lẹ́yìn tí ó di olókìkí ní oṣù kẹwàá ọdún 2012 nípasẹ̀ ìṣàfihàn rẹ̀ nínú orin àdákọ tí àkọ́lé rè ń jẹ́ latch èyí tó ṣipò kọkànlá lórí atọ́ka singles uk wọ́n sì padà ṣàfihàn orin naughty boy tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ la la ...
aubrey plaza aubrey christina plaza tí wọ́n bí ni june 26 1984 jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà aláwàdà àti olùdárí ó kópa gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn april ludgate lórí nbc sitcom parks àti recreation láti 2009 2015 àti ìfihàn rẹ̀ nínú jara eré fx legion 2017 2019 ní ọdún 2022 ó kópa nínú eré àkọ́kọ́ tó jẹ́ apá keji antholog...
meghan trainor meghan elizabeth trainor tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kejìlá ọdún 1993 ọmọ orílẹ̀-èdè america jẹ́ gbajúgbajà olórin ó di gbajú-gbajà lẹ́yìn tí ó fọwọ́ sí ìwé pẹ̀lú epic records ní ọdun 2014 tí ó sì ko orin rẹ̀ àkọ́kọ́ tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ all about that bass ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn orin tí àwọn ará amerika ...
iko ikọ́ jẹ́ ohun tí ó máa ń wáyé láti mú ikun àti ìdọ́tí bíi eruku tàbí èéfín kúrò ní àyà wa ikọ́ fún ra rẹ̀ kìí se àìsàn ṣùgbọ́n wíwú ikọ́ léraléra lè jẹ́ àmì wípé àìsàn wà lára ikọ́ jẹ́ ọ̀kan lára nkan tí ènìyàn ó ní agbára lé lórí kódà bí ènìyàn kò bá fẹ́ wúkọ́ bí ìdọ́tí tàbí àìtó bá ti wọ ọ̀nà ofun tàbí ẹ̀dọ̀fóró ...
omo kadara
ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbóhùngbáwòrán sáfẹ́fẹ́ tẹlifísàn ní nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbóhùngbáwòrán sáfẹ́fẹ́ lè jẹ́ ìtòpasẹ̀ padà sí ìparí àwọn ọdún 1950 nígbàtí western region tẹ́lẹ̀ ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìfihàn tẹlifísàn àkọ́kọ́ ti nàìjíríà ní déédé ọdún 1959 ti sàmì ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésáfẹ́fẹ́ tẹlifísàn ní nàìjíríà pẹ̀lú western nigeria tel...
obianuju ekeocha nigerian biomedical scientist obianuju ekeocha tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí uju a bi ní odun 1979 jẹ́ onímọ̀ sáyẹ́nsì ọmọ orílè-èdè nàìjíríà tí ó ń gbé ní ilẹ̀ọba aṣọ̀kan òun ni ọ̀lùdásílẹ̀ àti ààrẹ culture of life africa ìtàn rẹ̀ ekeocha ń gbé ní orílẹ̀ èdè ilẹ̀ọba aṣọ̀kan ẹ̀ka ibi tí ó ti ń síse ni ẹ̀ka àwọ...
anthonia kẹ́hìndé fátúnsìn
iroro tanshi iroro tanshi tí a bí ní ọdun 1984 tàbí 1985 jẹ́ ọmọ nàìjíríà tí ó ní òye lọ́pọ̀lopọ̀ nípa àwọn àdán ó sì ń kó nípa àwọn oríṣiríṣi ẹ̀yà àdán ní afrika ó wà lára àwọn ọ̀lùdásílẹ̀ small mammal conservation organisation smacon
maria stepanova akewi maria mikhailovna stepanova ọmọ orílẹ̀-èdè russia мари́я миха́йловна степа́нова tí a bí ní osù kẹfà ọjọ́ 9 ọdún 1972 jẹ́ akéwì ará ìlú russia òǹkọ̀wé àti oníròyìn ó jẹ́ olóòtú ti coltraru lọ́wọ́lọ́wọ́ èyí tó jẹ́ ìwé àtẹ̀jáde orí ayélujára tí ó dá lórí àṣà àti iṣẹ́-ọnà ní ọdún 2005 ó gba àmì-ẹ̀yẹ a...
àtòjọ orúkọ àwọn obìnrin nigeria onímọ̀ sáyẹ́ǹsì
francisca oboh ikuenobe francisca oboh-ikuenobe jẹ́ onímọ̀ sáyẹ́ǹsì ti ẹ̀ka-ìmọ̀ nípa ayé is a geology ọmọ ubiaja ní ìjọba-ìbílẹ̀ esan south east local government ti ìpínlẹ̀ ẹdó ìmọ̀ ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ni palynology àti sedimentology bẹ́ẹ̀ náà ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ni ẹ̀ká-ẹ̀kọ́ geosciences and geological and petroleum and engi...
deborah ajakaiye wọ́n bí deborah enilo ajakaiye ní ìpínlẹ̀ plateau ní apá àríwá nàìjíríà ní ọdún 1940 bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ onímọ̀ nípa físíìsì ilé-ayéorilẹ̀-èdè nàìjíríà òun ní obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ́ ọ̀jọ́gbọ́ nínú físíìsì ní ilẹ̀ áfíríkà iṣẹ́ rẹ̀ nínú ìmọ̀jẹ́mọ́ físíìsì ilé-àyé tí ran orílẹ̀-èdè yìí lọ́wọ́ nínú ìwàkùsà ìb...
temie giwa-tubosun oluwaloni olamide giwa tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí temie giwa-tubosun tí a bí ní oṣù kejìlá ọdún 1985 jé ọmọ orílè-èdè nàìjíríà mọ́ amẹ́ríkà tí ó ní ìmò nípa ètò ìlera òun ní ọ̀lùdásílẹ̀ life bankilé-isé tí wón ń pè ní one percent project ilé-isé kan ní nàìjíríà tí ó ń síse takuntakun láti ri si ilo wọ́rọ́w...
janet edeme janet edeme jẹ́ onímọ̀ sáyẹ́ǹsì tó ní ṣe pẹ̀lú ohun ọ̀gbìn ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti onímọ̀ ìjìnlẹ̀ nínú ohun ọ̀gbìn tí ó ṣiṣẹ́ bí olùdarí ẹ̀ka rural economy and agriculture at the african union commission - auc/drea tí ó wà ní addis ababa ilẹ̀ ethiopia auc/drea jẹ́ ẹ̀ka kan láàrín ìṣọ̀kan áfíríkà tí ó ní ...
ebun oni professor ebun oni tí a bí ní ọjọ́ 21 oṣù karùn-ún ọdún 1935 -tí ó sì di olóògbé ní ọjọ́ 2 oṣù kejìlá ọdún 2021 ni a mọ̀ sí ebun adegbohungbe nígbà ayé rẹ̀ tí ó wá padà di ebun adefunmilyo oni orúkọ ọkọ rẹ̀ ó jé onímọ̀ sáyẹ́ǹsì tó ń fi ohun àfojúrí fi kẹ́kọ̀ọ́ nípa ayé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ni ó jẹ́ olùkọ́ n...
helen asemota helen nosakhare asemota jẹ́ baokẹ́mísítì àti baotẹkinọ́lọ́gísìtì nípa nǹkan ọ̀gbìn tó wà ní jamaica ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n fún baokẹ́mísítì àti mòlẹ́kúlà bìólójì àti ádárì fún sẹ́ńtà baotẹkinọ́lọ́gísìtì fún fáṣítì west indies ní mona jamaica àwọn ìwádìí rẹ̀ mú ìlọsíwájú bá baotẹkinọ́lọ́gísìtì nípa bí wọ́n ṣe má...
olúwatóyọ̀sí ògúnṣẹ̀yẹ
adeyinka gladys falusi adeyinka gladys falusi jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmò ẹ̀jẹ̀ àti omi ara ní nàìjíríà òun sì ni olùdarí tẹ́lẹ̀ rí fún ibi ẹ̀kọ́ advanced medical research and training college of medicine ti yunifásítì ìlú ìbàdàn ó ní ìmò púpò nínú àwọn àwọn àìsàn ẹ̀jẹ̀ tí ó ń pa ènìyàn lára ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ...
ijeoma uchegbu ijeoma uchegbu jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti ẹ̀kọ́ nípa ìmọ̀-oògùn ní university college london níbi tí ó ti dipò igbákejì ààrẹ mú fún ilẹ̀ adúláwọ̀ àti ààrin-gbùngùn ó jẹ́ nigerian-britih òun ni olóri oníṣẹ́ sáyẹ̀ǹsì ti nanomerics èyí tí ń ṣe ilé-iṣẹ́ tó ń ṣe oògùn láti wá ojútùú sí omi tí ò mọ́ òun sì ni gómìnà we...
rita orji rita oluchi orji jẹ́ ọmọ orílé-èdè nàìjíríà tí ó tún fi apá kan tan mọ́ kánádà ó jẹ́ onímọ̀ kọ̀m̀pútà fún kánádà nínú ìwádìí jinlẹ̀ fún ẹgbẹ́ pasuáfùù àti olùdarí pasuáfùù kòmpútí laàbù tí ilé ẹ̀kọ́ gíga yunifásítì dalhousie ìṣe rẹ̀ dá lé lórí bí a ṣe lè lo ìṣòro ǹ gbésì láàrin ènìyàn àti ẹ̀rọ kọ̀m̀pútà ó ti ...
lucy jumeyi ogbadu lucy jumeyi ogbadu tí a bí ní ọjọ́ àrùn-dín-lọ́gbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1953 jẹ́ onímọ̀ràn microbiologist ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó sì ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùdarí àgbà àti alákoso national biotechnology development agency nabda ilé-iṣẹ́ ìwádìí lábẹ́ ilé-iṣẹ́ ti ìmọ̀-jinlẹ̀ àti ìmọ̀-ẹ̀rọ ti nàìjíríà títí di...
grace oladunni taylor grace oladunni taylor tí a tún mọ̀ sí grace oladunni lucia olaniyan-taylor tí a bí ní ọjọ́ 24 oṣù kẹrin ọdún 1937 jẹ́ biochemist ní yunifásítì ìlú ìbàdàn nígbà kan rí òun ni obìnrin ẹlẹ́ẹ̀kejì tí wọ́n máa gbà wọlé sí nigerian academy of science àti obìnrin ilẹ̀ adúláwọ̀ àkọ́kọ́ láti gba àmì-ẹ̀yẹ̀ ...
rita orgi
omowunmi sadik omowunmi wunmi a sadik tí a bí ní ọjọ́ 19 oṣù kẹfà ọdún 1964 jẹ́ ọ̀jọ́gbọ́n orílẹ̀-èdè nàìjíríà onímọ̀ nípa oògún àti aṣèdásílẹ̀ ohun ọ̀tun tó ń ṣịṣẹ́ ní binghamton university ó ti ṣàgbékalẹ̀ microelectrode biosensors fún ṣíṣàwárí oògùn àti èròjà bọ́m̀bù ó sì ń ṣiṣẹ́ lórí ìdàgbàsókè àwọn ẹ̀rọ amáyẹrọrùn ...
arun iko
folakemi titilayo odedina folakemi titilayo odedinaèni tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélógún osù kín-ín-ní ọdún 1965 jẹ́ onímọ̀ sáyẹ́ǹsì orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti olùkọ́ àgbà ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ilẹ̀ floridauniversity of florida ó jẹ́ gbòógì atọpinpin fún the prostate cancer translantic consortiumcaptc ó tún jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ ame...
tapioca tapioca / / ˌtæp i ˈ oʊkə / portuguese portuguese tapiˈɔkɐ jẹ sitashi tí a fa jáde láti awọn gbongbo ibí ìpamọ tí ọgbin gbaguda manihot esculenta tí a tún mọ̀ ní manioc ẹyà abínibí sí awọn ẹkun ariwa àti àríwá ila-oorun tí brazil ṣùgbọ́n lilo rẹ tí tán káàkiri south america ní báyìí o jẹ abemiega perennial tí o...
àádùn àádùn jẹ́ oúnjẹ ipanu ìgboro tí o gbajúmọ̀ láàrin àwọn ìpínlẹ̀ yoruba ní nàìjíríà orúkọ àádùn túmọ sí adùn àti pé o tún máa n ṣẹ iranṣẹ ní ibi igbeyawo àti àwọn ayẹyẹ isọsọ akopọ àwọn èròjà mẹ́rin tí o wọpọ tí a lo fún ṣíṣe àádùn ní iyẹfun àgbàdo ata chilli èpo ọpẹ àti ìyọ́ oríṣi ipanu méjì lo wà tí wọn sì jẹ iyẹ...
oluwatoyin asojo oluwatoyin toyin asojo jẹ́ ásóṣíàtì pùròfẹ́sọ̀ àti alága fún ẹ̀ka-iṣẹ́ fún kẹ́mísítìrì àti baokẹ́mísítìrì ní fáṣítì hampton ó jẹ́ ásóṣíàtì pùròfẹ́sọ̀ ìgbà kan rí fún ìtọ́jú àwọn ọmọdé àti ìṣègùn ìgbà òrùn ní baylor college of medicine ó ṣiṣẹ́ máàtì kẹ́mísítìrì bàólógì kọnpútáṣọ̀nù ó jẹ́ kirisalogíráfà ...
uko nkole uko ndukwe nkole tí a bí ní ọjọ́ ogún oṣù kẹwàá ọdún 1975 ní ozu abam arochukwu ìpínlẹ̀ ábíá jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olóṣèlú nàìjíríà àti ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìgbìmò asofin nàìjíríà nkole ni aṣojú arochukwu/ohafia ní ilé ìgbìmò asofin kékeré ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí uko ndukwe nkole ní ọjọ́ ogún oṣù kẹwàá ọdún 1975 sín...
lasisi elenu nosa afolabi tí a mọ̀ sí lasisi elenu jẹ́ apanilẹ́rìn-ín òṣèré àti ohun tí àwọn olóyìbó mọ̀ sí compere látí offa ní ìlú kwara ní ilẹ̀ nàìjíríà ọ̀kan nínú àwọn èèyàn tó ní ipá olókìkí jùlọ ní áfíríkà ó jẹ́ olókìkí fún àwọn eré apanilẹ́rìn-ín ṣókí rẹ̀ pẹ̀lú àlẹmọ 'ẹnu jákéjádò' ní àkókò tó bá ń ṣeré àti lórí...
ogun wet ẹ crisis in nigeria ogun wet ẹ jẹ́ rògbòdìyàn ìfẹ̀hónúhàn tí ó bẹ́ sílẹ̀ láàárín nílẹ̀ yorùbá lápá iwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè nigeria láàárín àwọn ẹ̀yà hausa-fulani àti apá kan lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú nigerian national democratic party lásìkò ètò ìdìbò olóṣèlú àkọ́kọ́ tí ó fa ìdìtẹ̀-gbàjọba ológun àkọ́kọ́ ní nige...
uko nkole
aranso aránṣọ ni ẹnikẹ́ní tí ó ti yan láti máa so aṣọ pọ̀ tàbí se àtúnṣe aṣọ tí a ti rán tẹ̀lẹ̀bíí àpẹẹrẹ ẹ̀wù ṣòkòtò àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀lọ láti mú kí o ṣe déédé ẹni tí a dáa fún un aránṣọ gbúdọ̀ jẹ́ ẹni tí ó ti ní ìmọ̀ tẹ́lẹ̀ yálà kí ó ti kọ́ọ ṣáájú tàbí kí ó jogún báa lọ́wọ́ ìyá tàbí bàbá rè ẹnikẹ́ni tí ó bá ní ojú ọnà le...
ìfẹ́ àìlẹ́gbẹ́ ìfẹ́ àìlẹ́gbẹ́ jẹ́ ìfẹ́ tí kò ní gbèdéke tàbí tí kò ní àní-àní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ní ó ní ìtumò tí wón fún ìfẹ́ àìlẹ́gbẹ́ ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ gbàgbọ́ pé ó jẹ́ ìfẹ́ tí kò ní gbèdéke tí kò sì lẹ yí padà lábé oun tí ó bá wù kí ó ṣẹlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìgbàgbọ́ àwọn ẹ̀lẹ́sìn krístì gbàgbọ́ pé ìfẹ́ àìlẹ́gbẹ́ jẹ́ ọ̀kan nínú...
ugbo kingdom ìlú ùgbò jẹ́ ìlú ní ìjọba ìbílè ìlàjẹ ní ìpìnlẹ̀ oǹdó gúúsù-iwọ̀-oòrùn nàìjíríà àwọn apẹja ló pọ̀ jù lára àwọn ará ìjọba ùgbò ìṣàkóso ìjọba ùgbò ní àwọn ìdámẹ́rin mẹ́rìndínlógún ó sì ní olórí nípasẹ̀ àwọn olóyè tí a yàn gẹ́gẹ́ bíi àṣà àti ìṣe wọn ọkàn lára àwọn olórí ilé ẹgbẹ́ náà tí wọn ń pè ní olóyè gbóg...
ife north ife north je ọkàn nínú àwọn ìjọba ibile ín agbegbe osun state ní orílè èdè nigeria olú ilé rẹ wà ní ilu ipetumodu ni ariwa tó wà ní
ted dekker ted dekker tí a bí ní october 24 1962 jẹ́ onkọ̀wé ọmọ orílè-èdè america tó ko ìwé kirisiteeni alarameeriiri àti ìtàn alafinuro bii thr3e obsessed ati the circle series wón bí dekker ní netherlands new guinea láìpẹ́ lẹ́yìn tí wọ́n ti gbé e sí abẹ́ aṣẹ́ aláṣẹ fún ìgbà díẹ ní ìparapò àwọn orílẹ̀-èdè kó tó di ẹk...
ṣe idanilaraya a bí doh kyung-soo ní ọjọ́ kejìlá oṣù kìn-ín-ní ṣẹẹrẹ ní korea ọkùnrin yìí ni a tún mọ̀ sí tí do ó jẹ́ akọrin àti òṣeré south korea tí a mọ jùlọ bi ọmọ ẹgbẹ ti ẹgbẹ ọmọkùnrin south korea-chinese exo yàtọ̀ si àwọn iṣẹ́ ẹgbẹ rẹ d o tí ṣe eré ni ọpọlọpọ àwọn eré orí tẹlifisiọnu àti àwọn fiimu bíi pure love ...
lucy j ogbadu lucy jumeyi ogbadu ọjọ́ ìbí rẹ̀ ni ọjọ́ karúndílógbọ̀n oṣù kẹsàn ọdún 1953 jẹ́ ọmọ orílè-èdè nàìjíríà tí ó jẹ́ onímọ̀ nípa àwọn kòkòrò aifojuri pàápàá jùlọ àwọn tí ó ń fa àìsàn ósì ti ṣíṣe gẹ́gẹ́ bí adarí àgbà àti olùdásílẹ̀ ilé iṣé national biotechnology development agency nabda ilé iṣé tí ó ń ṣiṣẹ́ ìwàá...
abdulrahman abdulrazaq abdulrahman abdulrazaq tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kejì ọdún 1960 jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílè-èdè nàìjíríà ẹni tí ó jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ kwara láti ọdun 2019 òun ni alága télèrí ilé-isé first fuels limited ó dupò gómìnà ìpínlè ìpínlẹ̀ kwara ní 2003 2007 àti 2011 lábé ẹgbẹ́ òsèlú congress for progressive...
gèlè gèlè jé irúfé aṣọ tí a máa n gbá mọ́ orí kòsí aṣọ tí o leè wuyì-wúni-lórí lára obìnrin yorùbá láìsì gèlè gèlè ti wá di gbajú-gbajà láàrín àwọn obìrin ní gbogbo orílẹ̀-èdè wa nàìjíríà gèlè jẹ́ ǹkan pàtàkì tí ọmọ-bìnrin kìí fií falẹ̀ lọ́jọ́ ayẹyẹ ìgbéyàwo wọn bákannaáà ni àwọn alábáṣe kò gbẹ́hìn a sì tún se àmúlò rẹ...
joyce meyer american author born 1943pauline joyce meyer née hutchison june 4 1943 jẹ́ òǹkọ̀wé onígbàgbọ onígbàgbọ ọmọ amẹ́ríkà kan agbọ̀rọ̀sọ̀ àti alága tí àwọn mínísítà joyce meyer joyce àti ọkọ rẹ̀ dave pèlú àwon ọmọdé merin tun ti dàgbà gbé ní ìta st louis missouri iṣẹ́-ìránṣẹ́ rẹ̀ wà ní ilé-iṣẹ́ nítòsí agbègbè st ...
ashoka olókìkí ashoka olókìkí aka ashoka the great 304 bc si 232 bc jẹ ọba ilu índíà kan o jẹ ọba kẹta ti ijọba maurya o si ti wa ni kà awọn ti o tobi olori india ti lailai ní ijọba rẹ jẹ lati 269 bc si 232 bc ni india atijọ ijọba emperor ashoka wa lori pupọ julọ agbegbe india pakistan afiganisitani nepal ati banglades...
margaret adebisi sowunmi oníṣe botany ati environmental archaeologistmargaret adebisi sowunmi tí wọ́n ń pè ní jádesimi tí ọjọ́ ìbí rẹ̀ jẹ́ ọjọ́ kẹ́rìnlélógún oṣù kẹsán ọdún 1993 jẹ́ oníṣe botany ní orílé èdè nàìjíríà àti onímọ̀ nípa archaeology o jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n àti pùròfẹ́sọ̀ nínú iṣẹ palynology àti onímọ̀ àti oníṣe ìw...
betty aberlin betty aberlin ti a bi betty kay ageloff oṣu kejila ọjọ 30 ọdun 1942 ilu new york jẹ oṣere amẹrika kan akewi ati onkọwe o ni ipa deede lori eto awọn arakunrin smothers aberlin ṣiṣẹ lori ọpọlọpọ awọn eto tẹlifisiọnu o ṣere arabinrin aberlin ninu eree adugbo ogbeni rogers awọn ipa fiimu rẹ pẹlu iṣẹ ni dogma ...
grace lin grace lin jẹ akọwe ara ilu amẹrika ati alaworan ọmọde iwe akọkọ rẹ awọn ẹfọ ẹlẹgbinthe ugly vegetables ni a tẹjade ni ọdun 1999 o ti kọ iwe itan mẹrin ọdun ajathe year of the dog ọdun ekuthe year of the rat nibiti oke ti pade oṣupawhere the mountain meets the moon ati odò starry ti ọrunstarry river of the sky...
mary morrissey mary morrissey ti a bi ni 1949 jẹ onkọwe ara ilu amẹrika ati alapon fun aise iwa-ipa kariaye o jẹ onkọwe ti ṣiṣe aaye awọn ala rẹ building your field of dreams eyiti o sọ awọn ijakadi morrissey ati awọn ẹkọ lati igbesi aye ibẹrẹ rẹ o tun jẹ onkọwe ti ko kere ju titobi lọ no less than greatness iwe kan ni...
margret rey margret elizabeth rey ti a bi margarete elisabeth waldstein osu keérìndínlógún odun 1906 di oṣu kejila ọjọ kọ̀kan lé ní ogún ọdun 1996 jẹ onkọwe ati alaworan ara ilu amẹrika kan ti o jẹ ọmọ jamani ti a mọ dara julọ fun jara curious george ti awọn iwe aworan awọn ọmọde ti oun ati ọkọ rẹ ha rey ṣẹda lati 1939...
outboard motors ohun ti o wa outboard motors awọn mọto ti ita jẹ iru eto imudara ti a lo lati fi agbara fun awọn ọkọ oju omi wọn ti wa ni igbagbogbo gbe sori gbigbe tabi sẹhin ti ọkọ oju omi ati lo ẹrọ ijona inu lati tan ategun kan awọn ọkọ ayọkẹlẹ ti ita gbangba wa ni ọpọlọpọ awọn titobi ati awọn agbara agbara ti o wa...
patty aubrey patty aubrey jẹ onkọwe ara ilu amẹrika kan lati california o fowosowopo kọ ọbe adiẹ fun jara ọkànchicken soup for the soul series pẹlu ọbe adie fun ẹmi onigbagbọchicken soup for the christian soul asiwaju ti ifiagbara fun awon obirin aubrey fọwọsowọpọ ko iwe kan ti o ni ero si awọn obinrin nikan ọbẹ adiẹ f...
ìdìbò gbogbogbòò orílẹ̀-èdè nàìjíríà ti ọdún 2023 ìdìbò gbogbogbòò orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ọdún 2023 wáyé ní ọjọ́ karúndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 2023 láti dìbò yan ààrẹ ìgbàkejì ààrẹ àwọn aṣojú ilé ìgbìmò asofin àgbà àti ilé ìgbìmò asofin kékeré ní nàìjíríà ààrẹ nàìjíríà lọ́wọ́ lọ́wọ́ ààrẹ muhammadu buhari kò le du ipò ...
2023 nigeria election ìbò orílẹ̀-èdè nàìjíríà ti ọdún 2023 yóò wáyé ní rẹpẹtẹ ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì àti ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹ́ta ọdún 2023 ìdìbòyan ààrẹ àti igbá-kejì ààrẹ yóò wáyé ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ààrẹ lọ́wọ́ lọ́wọ́ muhammad buhari kò le díje nítorí gbèdéke àkókò rẹ̀ ti tó láfikún ìdìbòyan à...
idibo ni naijiria ìdìbò ní nàìjíríà jẹ́ àwọn ọ̀nà yíyan àwọn aṣojú sí ìjọba àpapọ̀ ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti oríṣiríṣi àwọn ìpínlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè olómìnira kẹrin nàìjíríà ìdìbò ní nàìjíríà bẹ̀rẹ̀ láti ọdún 1959 pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú oríṣiríṣi ó jẹ́ ọ̀nà ti yíyan àwọn olùdarí níbití àwọn ará ìlú ti ní ẹ̀tọ́ láti dìbò ...
ballot bálọ́tì jẹ́ ohun èlò ìdìbò fún ìbò dídì tí a sì lè rí gẹ́gẹ́ bí ẹyọ pépà tàbí bọ́ọ̀lù kékeré tí wọ́n máa ń lò fún ìbò ìkọ̀kọ̀ ó sábà máa ń jẹ́ bọ́ọ̀lù kékeré wo ìkọ̀sílẹ̀ òǹdíje tí wọ́n fi ń ṣàkọsílẹ̀ ìpinnu tí àwọn òǹdìbò ṣe ní orílẹ̀-èdè italy ní ẹgbẹ̀rún ọdún mẹ́rìndínlógún òǹdìbò kọ̀ọ̀kan máa ń lo bálọ́tì àt...
polling station ojúkò ìdìbò jẹ́ ibi tí àjọ elétò ìdìbò pèsè kalẹ̀ fún àwọn olùdìbò tí wọ́n sì gbé àpótí ìdìbò sí kí ètò ìdìbò náà ó lè rọrùn bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ojúkò ìdìbò sábà ma ń túmọ̀ sí odidi ilé tabí gbọ̀ngàn kan tí àwọn olùdìbò yóò kórajọ sí tí wọn yóò sì tó lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti dìbò amọ́ ojúkò ìdìbò gan gan ni ọ̀g...
inec card reader ẹ̀rọ ìyẹkáàdì-wò ti àjọ inec náà jẹ́ ẹ̀rọ oníná béléjá fún ìṣàrídájú ìdìbò tí wọ́n ṣe láti máa ṣàyẹ̀wò àwọn káàdì ìdìbò alálòpẹ́ pvcs tí àwọn àjọ tí ó ń bójú tó ètò ìdìbò ní gbogbo orílẹ̀-èdè inec ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n ṣe ẹ̀rọ ìyẹkáàdì-wò náà fún ètò ìdánimọ̀ ìdá ojúlówó òǹdìbò ṣáájú ìbò dídì mọ̀...
inec card reader
pufu pufu puff-puff gẹgẹbi a ti n pe ni nigeria jẹ ipanu ibile afirika ti a ṣe ti iyẹfun sisun pufu pufu tí wá ni ṣẹ tí esufulawa tí o ní awọn iyẹfun iwukara suga bota iyo omi ati eyin èyí tí o jẹ́ iyan àti kí o jìn sísun ní ewebe epo sí kàn tí n mú kàn burawun awọ yan lulú le ṣee lo ni ibi iwukara ṣugbọn iwukara jẹ wọ...
epa bimo ọbẹ̀ ẹpa tàbí ọbẹ ẹ̀pà jẹ́ ọbẹ ti a ṣẹ láti ẹpa nigbagbogbo pẹlú ọpọlọpọ àwọn èròjà mìíràn o jẹ oúnje pataki ti afirika ṣùgbọ́n o tún jẹun ní ila-oorun asia taiwan amẹ́ríkà pàápàá ní virginia àti àwọn àgbègbè mìíràn ní àyíká àgbáyé o tún wọpọ ní díẹ nínú àwọn agbègbè gẹgẹ bí argentina ariwa-oorun bolivia àti p...
obe ẹpa ọbẹ̀ ẹpa tàbí ọbẹ ẹ̀pà jẹ́ ọbẹ ti a ṣẹ láti ẹpa nigbagbogbo pẹlú ọpọlọpọ àwọn èròjà mìíràn o jẹ oúnje pataki ti afirika ṣùgbọ́n o tún jẹun ní ila-oorun asia taiwan amẹ́ríkà pàápàá ní virginia àti àwọn àgbègbè mìíràn ní àyíká àgbáyé o tún wọpọ ní díẹ nínú àwọn agbègbè gẹgẹ bí argentina ariwa-oorun bolivia àti pe...
assétou diakité assétou diakité tí a bí ní ọjọ́ kẹẹ̀dógún osù kejì ọdún 1998 jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá fún stade malien àti ẹgbẹ́ orílẹ̀-ède malian ó ṣe asojú mali ní bi afrobasket fún àwọn obìrin ní ọdún 2019
nkem akaraiwe nkem akaraiwe tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún osù kejìlá ọdún 1996 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède nàìjíríà fún first bank àti ẹgbẹ́ nàìjíríà ó kópa nínú ife àgbáyé eré bọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá ti àwọn obìrin ti ọdún 2018 2018 fiba women's basketball world cup
nkechi akashili nkechi akashili tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún osù kejì ọdún 1990 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá sínú agbọ̀n ti ilẹ̀ nàìjíríà fún first bank bc àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède nàìjíríà iṣẹ́ síse òkè- òkun ó kópa níbi afro2017 women's afrobasket
onome akinbode-james onome akinbode-james tí a bí ní ọjọ́ kẹ̀sán osù kẹta ọdún 2000 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá sínú agbọ̀n ti orílẹ̀-ède nàìjíríà ó ṣojú orílẹ̀-ède nàìjíríà ní bi fiba africa under-16 championship fún àwọn obìrin ó gbá bọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá sínú agbọ̀n ti ilé ẹkọ́ girama fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá...
babátúndé húnpẹ
fẹ́mi gbàjàbíàmílà
ibrahim ọláńrewájú láyọdé
babátúndé fáṣọlá
oderah chidom oderah obiageli chidom tí a bí ní ọjọ́ kẹsan osù keje ọdún 1995 jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ãláfọwọ́gbá sínú agbọ̀n ti ẹ̀ya nàìjíríà-amẹrika tí ó ńṣeré fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìrin ti orílẹ̀ède nàìjíríà chidom ní àwọn àbúrò méjì ọkùnrin kan tí ó ń jẹ́ arinze àti obìnrin kan tí ó ń jẹ́ amara ó lọ sí i...
ugo oha ugochukwu henrietta oha tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù keje ọdún 1982 ní houston texas jẹ́ agbábọ̀ọ̀lù aláfọwọ́gbá sínú agbọ̀n ti àwọn obìnrin ti nàìjíríà-amẹrika ó díje ní bi 2004 summer olympics pẹ̀lú ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù aláfọwọ́gbá sínú agbọ̀n ti àwọn obìnrin ti orílẹ̀-ède nàìjíríà ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga ...
rashidat sadiq rashidat odun sadiqtí a bí ní ọjọ́ kẹta osù kínní ọdún 1981 ní ìlú ìbàdàn jẹ̀ agbábọ́ọ̀lù omo orílẹ̀-ède nàìjíríà ó gbábọ́ọ̀lù ní ilẹ̀ amẹrika pẹ̀lú university of connecticut huskies àti oklahoma state cowgirls ó tún gbábọ́ọ̀lù pẹ̀lú ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìnrin orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní 2004 summer olymp...
patty aubery patty aubery jẹ onkọwe ara ilu amẹrika kan lati california o fowosowopo kọ ọ ọbe adiẹ fun jara ọkànchicken soup for the soul series pẹlu ọbe adie fun ẹmi onigbagbọchicken soup for the christian soul asiwaju ti ifiagbara awon obirin aubery fọwọsowọpọ iwe kan ti o ni ero si awọn obinrin nikan ọbẹ adiẹ fun ẹm...
olayinka sanni olayinka sanni tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún osù kẹjọ ọdún1986 jẹ́ ògbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù sínú agbọ̀n ti nàìjíríà-amẹrika a bí ní chicago heights illinois láìpẹ́ ni ó gbá bọ́ọ̀lù tí ó sì wà ní ipò àárín sí iwájú fún phoenix mercury ní bi wnba àti fún charleville-méz ní ìlú france - lfb iṣẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíg...
taiwo rafiu taiwo rafiu tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún osù kẹ̀fà ọdún1972 ní ìpínlẹ̀ èkó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá sínú agbọ̀n obìnrin ti ilẹ̀ nàìjíríà ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìlú oklahoma ní amẹrika pẹ̀lú ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá sínú agbọ̀n ti àwọn obìrin ti orílẹ̀-ède nàìjíríà ní bi
cecilia okoye cecilia nkemdilim okoye tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá osù kẹsán ọdún 1991 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-ède nàìjíríà tí a bí sí orílẹ̀-ède amerika tí ó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù sínú agbọ̀n ti nàìjíríà fún bbc etzella àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède nàìjíríà ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ a bí ní new york sí àwọn òbí tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-ède nàìjír...
oluchi okorie oluchi mercy okorie tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlọgbọ̀n osù kẹjọ ọdún 1981 ní ìlú èkó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù sínú agbọ̀n ti orílẹ̀-ède nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí tí ó gbábọ́ọ̀lù fún first bank bc àti ẹgbẹ́ orílẹ̀-ède nàìjíríà ó ṣe aṣojú nàìjíríà ní bi 2005 2006 àti 2007 fiba africa championship iṣẹ́ ìdárayá síse láti ogúnjọ́...
libianca libianca kenzonkinboum fonjití wọ́n mọ̀ sí libianca jẹ́ ọ̀kọrin afrobeat ti won bí sí kameroon tí ó sì ń kọrin ní ìlú amẹ́ríkà ó wà lára àwọn tí wọn díje lórí ètò tí wón ń pè ní the voice èyí tí o jẹ́ ìràn kàn ní ìlú amẹ́ríkà ní ọdún 2021 ó ti ìpasẹ̀ orin àkọ́kọ́ tí tí ó pè ní people tí ó fí di olókìkí ní ọdún...
oxlade nigerian afro-fusion musician ikúforíjì oláìtán abdulrahman tí ayé mọ sí oxlade jẹ́ ọ̀kọrin àti olórin tí wà lábé ilé iṣé orin kàn ní orílé èdè faransé tí ó ń jẹ́ troniq music ẹ̀ka epic records àti ilé iṣé orin mìíràn ní uk tí orúko rẹ̀ ń jẹ́ fuenlabrada records ó di olókìkí nígbà tí orin tí ó pè ní away jáde tí...
godwin emefiele godwin emefiele tí a bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹjọ ọdun 1961 jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti gómìnà-àná ilé ìfowó pamọ́ àgbà nàìjíríà láti ọjọ́ kẹrin oṣù kẹfà ọdun 2014 títí di ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹfà ọdún 2023 tí ààrẹ bọlá ahmed tinubu pàṣẹ láti dá a dúró lẹ́nu iṣẹ́ nítorí ẹ̀sùn àwọn ìwà àjẹbánu kan...
alemitu tariku ethopian sprinter alemitu tariku olana ti a bini ọjọ kèji dinlọgbọn óṣu september ni ọdun 2000 jẹ elere to man sare fun idije ti ilẹ ethiópíà iṣẹ ati ipa àràbinrin naa alemitu kopa ninu idije agbaye ti ilu aarhus ni ọdun 2019 nibi ti arabinrin naa gba ami ẹyẹ ti silver ninu u20 ni iṣẹju 2050 lẹyin naa lo...
oríṣi ṣọ́ọ́ṣì àti àwọn ọ̀nà wọn kíló mú ilé ìjọsìn dúró kíni àwọn àmì àsọ̀yè àwọn àbùdá tí ó yà á sọ́tọ̀ èyí ni ohun tí a ó wò nínú ọ̀rọ̀ yìí àti ìṣọwọ́lò èdè wọn = ọ̀nà ilé ìjọsìn ti pẹ́ńtíkọ́sì = àkọ́kọ́ tí a ma yẹ̀ wò ni ìjọ tí a ń pè ní gẹ̀ẹ́sì ní pentecostal ó jẹ́ ọ̀nà kan ní ẹ̀sìn kìrìtẹ́nì tí ó tẹnumọ́ iṣẹ́ ti ẹ...
attahiru jega attahiru muhammadu jega tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kínní ọdún 1957 jé ọ̀mọ̀wé àti adarí yunifásítì báyéró tí ìpínlè kano tẹ́lẹ̀rí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹfà ọdun 2010 ààrẹ goodluck jonathan yanpẹ̀lú ìfọwọsí ilé ìgbìmò asòfin gẹ́gẹ́ bi alága independent national electoral commission inec ajo tí ó ń rí si ètò ì...
daniel nathaniel nigerian volleyball player daniel nathanieltí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù keje ọdun 1992 jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọkùnrin eléré ìdáyará volleyball tó gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ sunshine apikers ti akure ní orílẹ̀-èdè nàíjíría igbèsi aye arakunrin naa daniel kaweja pẹlú electrical electronic engineering to ṣèrè gẹgẹ...
amina zakari amina bala zakari tí a bí ní ọjọ́ kẹtalélógún oṣù kẹfà ọdun 1960 jẹ́ alága aájò àjọ elétò ìdìbò lorílẹ̀-èdè nàìjíríà inec tẹ́lẹ̀rí ìyàn sípò rẹ̀ fìdí múlè ní ìgbà tí ààrẹ muhammadu buhari fi sí ipò náà lẹ́yìn tí sáà attahiru jega wá sí ìparí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù keje ọdun 2015 zakari ni obinrin àkọ́kọ́ tí ó ...
bhimrao ramji ambedkar bhimrao ramji ambedkar april 14 1891 december 6 1956 je oloye ara india adajo onimo eto-aje oloselu onkọwe onimoye ati alatunse awujo o jẹ aṣáájú-ọnà ni ija fun awọn ẹtọ ti ẹhin ati imudogba awujọ ni india o ṣe atilẹyin ẹgbẹ dalit buddhist o si ṣe ipolongo lodi si iyasoto ti awujọ lodi si awọn ai...
mide martins nigerian actressmide funmi martins jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àwòṣe àti aṣàgbéjáde eré ó jẹ́ ọmọ òṣèrébìnrin funmi martins tí ó kú nípa àrùn ọkàn ní ọdún 2002 iṣẹ́ rẹ̀ mide martins bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ lẹ́yìn ikú ìyá rẹ̀ ní ọdún 2002 láti ìgbà náà ó ṣe àfihàn nínú fíìmù àgbéléwò lóríṣiríṣi ó sì ṣàgbéjáde àwọn ère lórí...
teniola aladese nigerian actressteniola aladese jẹ́ òṣèrébìnrin orílẹ̀-èdè nàìjíríà aṣàgbéjáde eré àti olùdarí eré ìgbésí ayé rẹ̀ a bí téníọlá aládaṣe sí ìpínlẹ́ èkó ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa mass communication ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga covenant iṣẹ́-ṣíṣe rẹ̀ teniola aladese ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi alábòójútó aṣàgbéjáde fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù...
isaac teitei nortey us-based ghanaian tennis player isaac teitei nortey jẹ elere tennis ta bi ni ọdun 1999 ti órilẹ ede ghana to sin gbe ni us ni ọmọ ọdun marun dinlogun isaac jẹ ọdọmọde elere to pegede julọ ninu idije junior tennis ti ilẹ afirica igbèsi aye elere naa nortey ni a bi si accra ghana oun kẹkọ lori igbega ...
yohanis algaw ethopian sprinter yohanis algaw ni a bini ọjọ kẹrinla óṣu august ni ọdun 1999 jẹ ẹ̀ni to ma n sarè fun ilẹ ethiopia igbèsi aye arakunrin naa yohanis ti a bi si ilẹ ethiopia kopa ninu óriṣiriṣi idije ilẹ̀ afirica ninu wọn ni idije caa senior ti ilẹ afirica ni ọdun 2022
edwin gadayi ghanaian sprinter edwin kwabla gadayi ti a bini ọjọ kẹrinla óṣu february ọdun 2001 jẹ asare fun ilẹ ghana arakunrin naa kopa ninu ere idije ti awọn asare to waye ni silesia poland ni ọdun 2021 nibi to ti wa lara awọn team ọkunrin marun igbèsi aye edwin gadayi gbe ni ashanti ghana to si lọ si ilè iwè giga t...
adebimpe oyebade adebimpe oyebade tí a bí ní 23 oṣù kẹta 1992 tí a mọ̀ sí mo bimpe jẹ́ òṣèré fíìmù nàìjíríà tí a mọ̀ fún gbígba àmì-ẹ̀yẹ ti ọdún 2018 ní city people entertainment awards gẹ́gẹ́ bíi òṣèré titun titun ti ọdún náà
murjanatu musa murjanatu liman musa tí a bí ní ọjọ́ kaàrún osù kaàrún ọdún 2000 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù sínú agbọ̀n orílẹ̀-ède nàìjíríà tí ó ń gbá bọ́ọ̀lù lọ́wọ́lọ́wọ́ fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù air warriors ti nàìjíríà àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède nàìjíríà isẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n tí ó yàn láàyò murjanatu gbábọ́ọ̀lù lọ́wọ́lọ́wọ́ pẹ̀lú ...
upe atosu upe atosu tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélọ́gún oṣù kẹ̀rin ọdún 1993 jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù inú agbọ̀n orílẹ̀-èdè nàìjíríà fún butler bulldogs bọ́ọ̀lù inú agbọ̀n ti àwọn obìnrin àti ẹgbẹ́ agbá bọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó kópa níbi 2017 women's afrobasket