raw_text
stringlengths
2
128k
martina ohadugha nigerian footballer martina ohadugha jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 5 óṣu may ni ọdun 1991 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun river angels
ngozi eucharia uche ngozi eucharia uche jẹ ọkan lara agbabọọlu obinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 18 óṣu june ni ọdun 1973 arabinrin naa jẹ agbabọọlu lobinrin tẹlẹ ri ti o si jẹ ólóri coach tẹlẹ ri fun team apapọ awọn obinrin lori bọọlu
ann chiejine nigerian footballer ann chiejine jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini ọjọ keji óṣu february ni ọdun 1974 agbabọọlu naa jẹ goalkeeper fun team bọọlu apapọ awọn obinrin ilẹ naigiria
josephine chukwunonye nigerian footballer josephine chukwunonye jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 19 óṣu march ni ọdun 1992 agbabọọlu naa ṣere fum swedish damallsvenskan club kungsbacka dff gẹgẹbi defender
nkechi egbe nigerian former football forward nkechi egbe jẹ́ agbábọ́ọ̀lú lóbìnrin tẹlẹ rí fún órilẹ èdè nàìjíríà tí a bíní ọjọ́ karún óṣu kejì ni ọdun 1978 agbábọ́ọ̀lu náà ṣeré tẹlẹ rí fún team àpapọ àwọn obìnrin lórí bọ́ọ̀lú gẹgẹ bí ipò iwájú orward
desire oparanozie nigerian footballer desire oparanozie jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ́ ede naigiria ti a bini 17 óṣu december ni ọdun 1993 agbabọọlu naa ṣere fun super league awọn obinrin ilẹ chineese ati team apapọ ilẹ naigiria
ini-abasi umotong nigerian footballer ini-abasi umotong jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lóbìnrin ti órilẹ èdè nàìjíríà tí a bíní 15óṣu karùn ní ọdún 1994 agbábọ́ọ̀lú àlà f'ẹsẹ gbá náà ṣeré fún club lewes àti team àpapọ nàìjíríà
evelyn nwabuoku nigerian footballer evelyn nwabuoku jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lóbìnrin tí órilẹ èdè nàìjíríà tí a bíní 14 oṣù kọkànlá ní ọdún 1985 agbábọ́ọ̀lù àlà gbá fẹsẹ̀ náà ṣeré fún en avant de guingamp ti french division 1 fèminine àti team àpapọ àwọn obìnrin lórí bọ́ọ̀lù
ugo njoku nigerian footballer ugo njoku jẹ́ agbábọ́ọ̀lú lóbìnrin órilẹ èdè nàìjíríà tí a bíní 27 óṣu kọkàǹlá ní ọdún 1994 arábìnrin náà ṣeré fún croix savoie ambilly gẹgẹ bí defender
johnny drille john ighodaro tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù keje ọdún 1990 tí gbogbo èèyàn mọ sì johnny drille jẹ́ akọrin àti òǹkọrin tí nàìjíríà iṣẹ́ orin rẹ̀ di ohun mímọ̀ nígbà tí ó tún orin diʼja tí àkọlé rẹ jẹ awww kọ wọ́n tí gba gẹ́gẹ́ bí ara àwọn olórin mavin records ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀ a bí a sì tọ́ johnny dril...
perpetua nkwocha nigerian footballer perpetua nkwocha jẹ ọkan lára àwọn agbábọ́ọ̀lú-ẹlẹ́sẹ̀ lóbìnrin tí a bíní ọjọ́ kẹta oṣù kínní odún 1976 arábìnrin náà ṣeré tẹ́lẹ̀ rí fún swedish club sunnanå sk àtipé agbábọ́ọ̀lú náà jẹ́ captain tẹ́lẹ̀ rí fún team àpapọ àwọn obìnrin ilẹ̀ nàìjíríà lórí bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀
nkiru okosieme nkiru doris nk okosieme tí wọ́n bí ní ọjọ́ kínní oṣù kẹ̀ta 1972 ti jẹ́ adarí egbẹ́ bọ́ọ̀lù-afẹsẹ̀gbá àwọn obìnrin ti nàìjíríà super falcons tẹ́lè rí ó sì tún ti gbá agbede méjì pápá-bọ́ọ̀lù fún egbẹ́ agbábọ́ọ̀lù gbogbo àwọn obìnrin nàìjíríà tí ó ti hàn nínú ìdíje bọ́ọ̀lù àwọn obìnrin ti gbogbo àwọn ìlú à...
maureen mmadu maureen nkeiruka mmadu wọ́n bi ní ọjọ́ kèje oṣù karùn-ún 1975 jẹ́ olùtọ́nisọ́nà bọ́ọ̀lù-afẹsẹ̀gbá àti pé agbábọ́ọ̀lù agbedeméjì pápá-ìgbábọ́ọ̀lù ni tẹ́lẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i agbábọ́ọ̀lù ó ń ṣojú avaldsnes il lọ́wọ́lọ́wọ́ ọ̀kan lára ẹgbé bọ́ọ̀lù ìpín àkọ́kọ́ tó pinlẹ̀ sí etíkun ìwọ̀-oòrun norway ó tún ti gbá bọ́ọ...
phoebe ebimiekumo nigerian footballer phoebe ebimiekumo tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kìíní ọdún 1974 jẹ́ obìnrin àgbábọ́ọ̀lù orílé èdè nàìjíríà tó gbá bọ́ọ̀lù gẹ́gẹ́ bí dìfẹ́ńdà fún nàìjíríà ó wà lára àwọn ẹgbẹ́ tí wọ́n wà ní àjọyọ̀ ìdíje fífà tí ọdún 1991 àti 1995 1991 fifa women's world cup àti 1995 fifa women...
eberechi opara nigerian footballer eberechi opara jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 6 óṣu march ni ọdun 1976 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender fun team apapọ awọn obinrin ilẹ naigiria lori bọọlu
chi-chi igbo danish nigerian footballer chi-chi igbo jẹ agbabọọlu orilẹ́ ede naigiria ti a bini 1 óṣu may ni ọdun 1986 chi-chi jẹ elere super falcons tẹleri arabinrin naa ṣere gẹgẹbi ipo forward fun fortuna hjørring
richard ofori goalkeeper richard ofori ti a bi ni ọjọ kini oṣu kọkanla ọdun 1993 jẹ agbabọọlu ọmọ orilẹede ghana kan ti o ṣere fun orlando pirates ti south africa premier division ati ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede ghana gẹgẹ bi gooli ologba ọmọ ghana ofori lo akoko pupọ pẹlu westland fc ẹgbẹ pipin keji ni accra ṣaaju ki o d...
fortune makaringe fortune makaringe ti a bi ni ọjọ ketala osu karun ọdun 1993 jẹ agbabọọlu afẹsẹgba alamọdaju ti orilẹ-ede south africa ti o ngba aarin fun ẹgbẹ agbabọọlusouth africa premier division orlando pirates o tun gba bọọlu fun ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede south africa oun gba bọọlu tẹlẹ fun maritzburg united ti a ...
lyle lakay lyle lakay ti a bi ni ọjọ ketadinlogun oṣu kẹjo ọdun 1991 jẹ agbabọọlu afẹsẹgba orilẹ-ede south africa ti oun gba bọọlu afẹsẹgba fun mamelodi sundowns ni ajumọṣe bọọlu afẹsẹgba premier ise egbẹ agbabọọlu o jẹ ọmo ti ile-ẹkọ ọdọ supersport united o ni igbega si ẹgbẹ agbabọọlu akọkọ ni 2009 ṣugbọn o lo akoko r...
nathaniel bassey nigerian gospel musician nathaniel bassey jẹ́ olórin nàìjíríà olùdarí ìjọ a-fọn-fèrè àti a-kọ-orin ẹ̀mí tí ó gbajú-gbajà fún àwọn orin rẹ̀ imela oníṣẹ́ ìyanu àti ọlọ́wọ́gbọgbọrọ ó ń lọ the redeemed christian church of god ó sì ń darí ìjọ the oasis èkó ìjọ àwọn ọ̀dọ́ ti rccg kings court ní vi ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀...
celestina onyeka nigerian footballer celestina onyeka jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 15 óṣu july ni ọdun 1984 agbabọọlu naa ṣere fun pelican stars gẹgẹbi defender
akudo sabi nigerian footballer akudo sabi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 17 óṣu november ni ọdun 1986 arabinrin naa ṣere fun bayelsa queens gẹgẹbi defender
cecilia nku cecilia ngibo nku ti a bi ni ọjọ kerindinlogbon oṣu kẹwa ọdun 1992 jẹ agbabọọlu naijiria ti o gba fun egbe agbabọọlu rivers angels ti idije awọn obinrin naijiria nku gba bọọlu akọkọ rẹ ni ìdíje agbaye ni ọdun 2010 lakoko ti o nṣere fun nigeria ni 2010 fifa u-20 world cup women arabinrin naa wa lara ikọ agba...
ngozi ebere nigerian footballer ngozi ebere jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 5 óṣu august ni ọdun 1991 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹ̀bi defender fun club norwegia arna-bjørnar
ibubeleye whyte nigerian footballer ibubeleye whyte agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 9 óṣu january ni ọdun 1992 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹ̀bi goalkeeper fun rivers angels ti o si kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ naigiria
efioanwan ekpo nigerian footballer efioanwan ekpo jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 25 óṣu january ni ọdun 1984 agbabọọlu naa jẹ ọkan lara ọmọ ẹgbẹ awọn obinrin apapọ lori bọọlu
binta masi garba nigerian politician binta masi garba wọ́n bí i lọ́jọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹrin ọdún 1967 jẹ́ gbajúmọ̀ oselu pàràkòyí oníṣòwò àti àti aṣàkóso tí ó jẹ́ aṣòfin-àgbà tí ó ń ṣojú ẹkùn ìdìbò apá àríwá ní ìpínlẹ̀ adamawa láti ọdún 2025 ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́-òṣèlú all progressives congress apc bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ obìnrin...
mr real okafor uchenna victor tí gbogbo ayé mọ̀ sí mr real jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó wá láti ìpínlẹ̀ èkó ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé ẹ̀ mr real tí a tún mọ̀ sí real self ni a bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹjọ ní ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà sí àwọn òbí tí ó wá láti ìlú okija ìpínlẹ̀ anámbra ó di gbajúgbajà lẹ́yìn tí ó...
mercy achieng kenyan footballer born 1992 mercy achieng jẹ agbọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 12 óṣu august ni ọdun 1992 agbabọọlu naa ṣere fun thika queens ati team apapọ ilẹ kenya
wendy achieng kenyan footballer wendy achieng jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 12 óṣu september ni ọdun 1993 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender
mwanalima adam kenyan footballer mwanalima adam jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 4 óṣu september ni ọdun 1997 agbabọọlu naa ṣere fun hakkarigücü spor ni super league awọn obinrin ilẹ turkey gẹgẹbi forward
lilian adera kenyan footballer lilian adera jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 7 may ni ọdun 1994 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender fun team apapọ awọn obinrin ilẹ kenya
stella ahono kenyan footballer stella ahono jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti o ṣere fun zetech sparks fc gẹgẹbi goalkeeper
mercy airo kenyan footballer mercy airo jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 20 óṣu october ni ọdun 1999 agbabọọlu naa ṣere fun kisumu all starlets fc gẹgẹbi forward
victorien adebayor adebayor zakari adje ti a bi ni ọjọ kejila oṣu kọkanla ọdun 1996 jẹ agbabọọlu ọmọ orilẹ-ede niger ti o gba fun ẹgbẹ agbabọọlu niger premier league usgn ti o wa la'win lati ọdọ danish 1st division club hb køge ni ọdun 2016 adebayor ni awọn idanwo pẹlu awọn ẹgbẹ kan ni ligue 1 fc lorient ati as monaco ...
boushaki boushaki lárúbáwá ‎ le tọka si
bernardo manuel bernardo manuel ti a bi ni o osu ketadinlogbon ni oṣu kejila ọdun 1954 jẹ asare olona-jinjin ara orilẹ-ede angola o dije ninu ìdíje mita 5000 awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1980
antónio dos santos athlete antónio dias dos santos ti a bi ni ọjọ keta oṣu kẹsan ọdun 1964 jẹ olufo gigun ti orilẹ-ede angola ati jumper olopometa ni ìdíje ere 1987 central african o gba ami-eye goolu ni fo olopometa ati ami ẹyẹ fadaka ni ti ifo gigun ni ipari idije naa ni 1988 ti afirika o gba ami-eye goolu ni fo olop...
marcos daniel swimmer marcos daniel ti a bi ni ọjọ kini oṣu kẹjọ ọdun 1961 jẹ oluwe omi fun orilẹ-ede angola o dije ninu awọn ìdíje meji ni olimpiiki igba ooru 1980
mario ervedosa mario ervedosa ti a bi ni ọjọ kejidinlọgbọn oṣu kaarun ọdun 1998 jẹ oluwe odo orilẹ-ede angola o dije ninu idije 50 mita igbaya ọkunrin ninu idije aquatics world 2017
vivaldo fernandes vivaldo fernandes ti a bi ni ọjọ kewa osu okudu ọdun 1971 jẹ oluwe odo orile-ede angola o dije ninu idije olufayawe 100 mita awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1988
gaspar fragata gaspar fragata ti a bi ní ọjọ kerin oṣu keji ọdun 1972 jẹ oluwe odo fun orilẹ-edeangola o dije ninu iwe onigbaya 100 mita awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1988 awọn itọkasi fç
daniel francisco daniel francisco ti a bi ni ọjọ kẹjo ọsu keji ọdun 2000 jẹ oluwe-odo fun orilẹ-ede angola o dije ninu ìdíje oni labalaba mita 50 ti awọn ọkunrin ni idije aquatics world 2017 ni ọdun 2019 o ṣe aṣoju angola ni ere afirika 2019 ti o waye ni rabat morocco
jorge gomes swimmer jorge gomes ti a bi ni ọjọ ketadinlogun oṣu kini ọdun 1972 jẹ oluwe-odo fun orilẹ-ede angola o dije ninu ìdíje ọkunrin 100 mita labalaba ni olimpiiki igba ooru 1988 ti o pari nikẹhin ni ipo 51st
salvador gordo salvador vieira gordo ti a bi ni ọjọ keje oṣu kini ọdun 2003 jẹ oluwe-odo fun orilẹ-ede angolan o dije fun angola ni olimpiiki igba ooru 2020 ni ipele labalaba 100m ti awọn ọkunrin o pari ni ipo 54th lapapọ pẹlu akoko 5596 ninu ooru rẹ o ti pinnu lati wa pelu iwẹ odo wiwẹ ni university of tampa ni orilẹ-...
luis matias luis matias ti a bi ni ọjọ kakandinlogbon osu kẹsán odun 1986 ni luanda jẹ oluwe odo angola kan ti o ṣoju angola ni olimpiiki igba ooru 2004 ni ipele labalaba 100 mita awọn ọkunrin lakoko o bori ipele ooru akoko pẹlu akoko 5892 o pari ni ipo 58th ninu awọn aaye 60 ati pe ko ni ilọsiwaju
pedro pinotes pedro miguel pinotes tí a bí ní ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù kẹsàn-án ọdún 1989 jẹ́ olùwè-odò orílẹ̀-èdè angola tí ó díje nínú ìdíje 400m ti àwọn ọkùnrin ni òlíḿpíkì ìgbà ooru 2012 ó parí ní ipò 30th lápapọ̀ nínú ìdíje ooru ní ìdíje oníkálùkù ti àwọn ọkùnrin 400 àti ó sì tún kùnà láti dé òpin-ìparí ní òlíḿpíkì ìgbà oo...
dário antónio dário antónio marcelino ti a bi ni ọjọ kejilelogun oṣu kẹwa ọdun 1992 jẹ ẹlẹṣin orilẹ-ede angola ti o gun lọwọlọwọ fun ẹgbẹ uci continental baisicasalpetro de luanda
igor silva cyclist igor alberto secundino silva tí a bí ni ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹwàá ọdún 1984 jẹ́ ẹlẹ́ṣin-ije ní òpópónà ní orílẹ̀-èdè angola tí ó gùn lọ́wọ́lọ́wọ́ fún ẹgbẹ́ uci continental baisicasalpetro de luanda
esse akida kenyan footballer esse akida jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 18 óṣu november ni ọdun 1992 agbabọọlu naa lọwọ ṣere fun poak ni ilẹ greece o wa lara awọn ọmọ ẹgbẹ harambee starlets
samantha akinyi kenyan footballer samantha akinyi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 6 óṣu january ni ọdun 1995 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi goalkeeper fun awọn ọdọmọbinrin makolander fc
vivian akinyi kenyan footballer vivian akinyi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 20 óṣu may ni ọdun 1994 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi goalkeeper
lucy akoth kenyan footballer lucy akoth jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 12 óṣu december ni ọdun 1999 agbabọọlu naa ṣere fun mathare united fc gẹgẹbi defender
lydia akoth kenyan footballer lydia akoth jẹ̀ agbabọọlu lobinrin orilẹ ede kenya ti a bini 22 óṣu september ni ọdun 1994 agbabọọlu naa ṣere fun thika queens fc gẹgẹbi midfielder
ann aluoch kenyan football player and manager ann aluoch jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kẹnya ti a bini 5 óṣu january ni ọdun 1990 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender
rosemary aluoch kenyan footballer rosemary aluoch jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 7 óṣu may ni ọdun 1976 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi goalkeeper ti o si ku si ilu kasarani ni ọjọ kẹrin óṣu october ọdun 2020 àṣeyọri rosemary ṣere fun team awọn obinrin ilẹ kenya lati 1995 si 2014 ni ọdun 2015 agbabọọlu naa d...
elizabeth ambogo kenyan footballer elizabeth ambogo jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 28 óṣu july to waye ni ọdun 1990 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender
sheril angachi kenyan footballer sheril angachi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini ọjọ akọkọ óṣu january ni ọdun 2000 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun gaspo youth fc àṣeyọri sheril kopa ninu nations cup awọn obinrin ilẹ́ afirica to waye ni ọdun 2018
carolyne anyango kenyan footballer carolyne anyango jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 27 óṣu february ni ọdun 1989 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi midfielder
doris anyango kenyan footballer doris anyango jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 19 óṣu november ni ọdun 1993 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹ́bi defender
fagrie lakay fagrie lakay ti a bi ni ọjọ kankanlelogbon oṣu karun ọdun 1997 jẹ agbabọọlu afẹsẹgba fun orilẹ-ede south africa ti oun gba siwaju fun ẹgbẹ agbabọọlu premier league egypt pyramids fc ati ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede south africa career statistics ti a bi ni manenberg lakay bẹrẹ bọọlu afẹsẹgba fun real stars ẹgb...
ayoko ayokunle olushola ayoko ayokunle olushola jẹ agbẹjọro ti a mọ daradara ni orilẹ-ede naijiria onisọwe idaraya pẹlu awọn ọdun ti iriri akojọpọ ọpọlọpọ awọn ile-iṣẹ ni ibamu ilana imọran ofin iṣakoso adehun iṣẹ ajọ / iṣowo iṣakoso ẹjọ iṣakoso ile-iṣẹ ilana ile-iṣẹ ati adaṣe ibamu nipa abi ọgbẹni ayoko ayokunle olush...
veli mothwa veli mothwa ti a bi ni ọjọ kejila oṣu kejí ọdun 1991 jẹ agbabọọlu afẹsẹgba fun orilẹ-ede south africa kan ti o n gba bọọlu bi gooli fun ẹgbẹ south africa premier division amazulu ati ẹgbẹ orilẹ-ede south africa o gba boolu akọbi rẹ fun orilẹ-ede south africa ni ọjọ kefa oṣu keje odun 2021 ninu ifẹsẹwọnsẹ wọ...
mercyline anyango kenyan footballer mercyline anyango jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 30 óṣu april ni ọdun 1995 agbabọọlu naa ṣere fun vihiga queens gẹgẹbi midfielder
neddy atieno kenyan footballer neddy atieno jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 8 óṣu july ni ọdun 1992 arabinrin naa ṣere fun ulinzi gẹgẹbi forward
cheris avilia kenyan footballer cheris avilia jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 11 óṣu december ni ọdun 1989 agbabọọlu naa ṣere fun spedag
lilian awuor kenyan footballer lilian awuor jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 13 óṣu june ni ọdun 1999 agbabọọlu naa ṣere fun harambee starlets
janet bundi kenyan footballer janet bundi jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 15 óṣu december ni ọdun 1996 agbabọọlu naa ṣere fun vihiga queens gẹgẹbi defender
sharon bushenei kenyan footballer sharon bushenei jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 7 óṣu june nì ọdun 1988 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi forward
vivian corazone kenyan footballer vivian corazone jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 2 óṣu october ni ọdun 1998 agbabọọlu naa ṣere fun gaspo youth gẹgẹbi midfielder
lamia essaadi lamia essaadi ti a bi ni ọjọ keta oṣu kẹwa ọdun 1979 jẹ agba tẹnisi lati orilẹ-ede morocco essaadi ni ipo wta ti o gaa pẹlu ami 469 ni alailẹgbẹ ti o gba ni ọjọ ogbon oṣu kẹrin ọdun 2001 ati 398 ni ilọpomeji ti o gba ni ọjọ kẹsán oṣu kọkanla ọdun 1998 o ti gba ipo kini ni ti ẹyọkan ni circuit awọn obirin ...
terry engesha kenyan footballer terry engesha jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 15 óṣu february ni ọdun 1998 agbabọọlu naa ṣere fun south korean club red angels wfc
ruth ingosi kenyan footballer ruth ingosi jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 19 óṣu december ni ọdun 1993 agbabọọlu naa ṣere cypriot club lakatamia fc gẹgẹbi defender
wincate kaari kenyan footballer wincate kaari jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 13 óṣu november ni ọdun 1999 agbabọọlu naa ṣere fun thika queens fc gẹgẹbi defender
mr eazi ọjọ́ kankàn-dín-lógún oṣù agẹmọ ọdún 1991 ní wọn bí oluwatosin ajibade tí orúkọ ìnàgijẹ rẹ̀ ń jẹ́ mr eazi olórin ilẹ̀ nàìjíríà ni bẹ́ẹ̀ náà ni ó jẹ́ òǹkọrin àti oníṣòwò ó jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tí ó dá orin banku iyẹn àpapọ̀ ohùn orin ghana àti ilè nàìjíríà mr eazi kó lọ sí kumasi ní orílẹ-èdè ghana ní ọdún 2008 ó sì ...
yusuf maart moegamat yusuf maart ti a bi ni ọjọ ketadinlogun oṣu keje odun 1995 jẹ agbabọọlu south africa ti o n gba iwaju fun ẹgbẹ south africa premier division sekhukhune united ati ẹgbẹ orilẹ-ede south africa ise egbẹ agbabọọlu orlando pirates maart ni a bi ni cape town o si dagba ni atlantis orlando pirates ṣe akiy...
jules bessan jules yao bessan ti a bi ni ọjọ kerinla oṣu kẹrin odun1979 je oluwe-odo ti orilẹ-ede beninese o se oju orilẹ-ede re ni idije 2016 summer olympics ni 50 mita elere o gbe ipo 77th pẹlu asiko 2732 iseju aaya ko yanjun si ipele ti o kangun si asekagba bessan si ni eniti ami eye orilẹ-ede benin ninu 50 mita ele...
alois dansou aloïs dansou ojoibi 1982 je olowe olimpiiki lati ilu benin o we fun orilẹ-ede benin ni amon ìdíje wonyi
christophe pognon christophe pognon ti a bi ni ọjọ kankanla oṣu kẹwa ọdun 1977 ni cotonou jẹ oṣere tẹnisi tẹlẹ lati benin pognon ṣe aṣoju orilẹ-ede abinibi rẹ ni olimpiiki igba otutu 2000 ni sydney australia nibiti o ti ṣẹgun ni ipele akọkọ nipasẹ gustavo kuerten brazil eni ti o ni ọwọ ọtun de ami iyasọtọ atp ti o ga j...
aloÿs nizigama aloÿs nizigama ti a bi ni ọjọ kejidinlogun osu okudu ọdun 1966 jẹ asare olona jinjin ọmọ ilu orilẹ-ede burundi ti o ti fẹhinti ti o iṣe re je ti mita 5000 ati 10000 ninu iṣẹ rẹ nizigama sa ere-ije ni iṣẹju 21 ati iṣẹju-aaya-28 ni 10000 mita ni ipo keji si haile gebrselassie pẹlu akoko 23
nosa omoregie ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa the nigerian recording artiste fún other uses ẹ wo nosa omoregie nosa omoregie tí a mọ̀ mọ́ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i nosa jẹ́ oníṣẹ́-ọnànàìjíríà olórin a-kọ-orin àti eléré ó wà lábẹ́ warner music group african partner lọ́wọ́lọ́wọ́ chocolate city ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé-ayé nosa omoregie tí w...
mary kinuthia kenyan footballer mary kinuthia jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 19 óṣu february ni ọdun 1990 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi forward
annette kundu kenyan footballer annette kundu jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 17 óṣu december ni ọdun 1996 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi goalkeeper
sylvia lumasia kenyan footballer sylvia lumasia jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ́ kenya ti o ṣere fun ile ẹkọ lori bọọlu ọdọmọbinrin kibera gẹgẹbi forward
enez mango kenyan footballer enez mango jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini ọjọ akọkọ óṣu july ni ọdun 1993 agbabọọlu naa ṣere fun vihiga queens fc gẹgẹbi left wing back
rachael muema kenyan association football player rachael muema jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 6 óṣu october ni ọdun 1999 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun thika queens fc
doreen nabwire kenyan former footballer manager and executive doreen navwire jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 5 óṣu march ni ọdun 1987 arabinrin naa ṣere fun pec zwolle fc gẹgẹbi midfielder
christine nafula kenyan footballer christine nafula jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 10 óṣu november ni ọdun 1991 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi midfielder
vivian nasaka kenyan footballer vivian nasaka jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 19 óṣu december ni ọdun 1999 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi defender fun vihiga queens fc
adebisi akanji nigerian artist adebisi akanji ibí 1930 jẹ́ òṣèré tí orílé èdè nàìjíríà bákan náà ó sí jẹ́ olóyè olúwo ògbóni tí ilé ìlédì kàrún ohùntótó èyí tí ó jẹ́ ògbóni tí ó jẹ́ gbóògì tí ìbílẹ̀ lodge tí ìlú òṣogbo ní ìpìnlẹ̀ ọṣun ní orílé èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ìwé kíkà ní gbà tí ó gbọ́njú ọ ṣíṣe gẹ́gẹ...
lorna nyarinda kenyan footballer lorna nyarinda jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 13 óṣu october ni ọdun 2000 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun vihiga queens fc
sunday jack akpan nigerian sculptor sunday jack akpan orúkọ ìbisọ rẹ ni ikot ide etukudo 1940 jẹ́ agbẹ̀gí kéré tí orílé èdè nàìjíríà tí wón ń pé ní èdè gèésì ni the contemporary african equivalent of the medieval artisan ó jẹ́ gbajúmò fún iṣé rẹ̀ iṣé ère èyí tí ó máa ń ló sìmẹ̀tì cement èyí tí ó máa ń fí ń gbé àwọn èrè...
jacky ogol kenyan footballer jacky ogol jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini ọjọ keji óṣu december ni ọdun 1994 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder
emmanuel taiwo jegede emmanuel taiwo jegede ti a bi ni june 1943 jẹ akewi ọmọ orilẹede naijiria akọwe itan oluyaworan atẹwe ati alaworan ninu igi idẹ ati seramiki ìbéèrè ayé rẹ àti ẹkọ emmanuel taiwo je omo bibi ilu ayegbaju ekiti a yoruba-speaking agbegbe ti naijiria ọ kó isé eré mimọ lati owo pa akerejola ni ekiti lẹ...
olowe of ise olowe of ise yoruba ọlọ́wẹ̀ ti ìsẹ̀ c 1873c 1938 ní èrò àwọn òpìtàn iṣẹ́-ọnà tí wọ́n jẹ́ òyìnbó àti àwọn olùgbàsílẹ̀ iṣẹ́-ọnà jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn tí ó ṣe pàtàkì jù ní sẹ́ntúrì 20 láàárín àwọn oníṣẹ́-ọnà ti àwọn ará yorùbá tí ó jẹ́ nàìjíríà òní áfíríkà ó jẹ́ agbẹ́gilére igi a-gbẹ́-ère àti ọ̀gá olùdásílẹ̀ ní...
felix idubor nigerian sculptor felix idubor 19281991 jẹ́ agbẹ́gilére nàìjíríà láti ìlú benin ìlú kan tí ó ní ìtàn tí ó lọ́ọ̀rìn nípa ìmọ̀ọ́ọ́ṣe iṣẹ́-ọnà ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹgbẹ́ kékeré àwọn oníṣẹ́-ọnà ní àárín 1950 àti 1960 tí wọ́n ṣe igbéǹde ìdálẹ́kọ̀ọ́ mímọ̀ nípa iṣẹ́-ọnà ìṣe áfíríkà ní dídé àti ní ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀wọ́ è...
irene ogutu kenyan footballer irene ogutu jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 14 óṣu june ni ọdun 1987 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender fun team apapọ awọn obinrin lori bọọlu
phoeby okech kenyan footballer phoeby okech jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 10 óṣu october ni ọdun 1994 agbabọọlu naa ṣere fun vihiga queens fc gẹgẹ̀bi midfielder
judith osimbo kenyan footballer judith osimbo jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 8 óṣu august ni ọdun 1999 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi goalkeeper fun awọn obinrin gaspo
nelly sawe kenyan footballer nelly sawe jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti oun ṣere fun thika queens fc gẹgẹbi defender