Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Díẹ díẹ l'Ọpẹ ń jẹe là.
1
Kò lè tún àtúnṣe fún ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ àti ọ̀kadà tó bàjẹ́.
0
Agbọ́nmi ní ń wólé ẹja; apàjùbà ní ń wólé àparò; òlùgbóńgbó tìǹlà ni wọ́n fi ń ṣẹ́gun ògúlùtu.
1
Àìlówó Ọ̀rúnmìlà, a ò lè fi wé ti Ẹlẹ́-gbára.
1
Wọ́n ní ọkùnrin náà kò láṣìírí.
0
Ó sọ pé àwọn ènìyàn máa ń yọ̀ mọ́ àwọn bí wọ́n bá rí àwọn nínú ọjà.
0
Ẹ̀hìn ní ń dun ol-ókùú-àdá sí.
1
Àgbẹ tó ń roko; tí 'ò gbin ẹgẹ; ó ń dawọ délẹ, ó ń dìde ni.
1
Ara ń dun pẹpẹ, eyìn ń dun àjà; òrùlé ni gbogbo ara 'ò jẹ tòun.
1
Àwọn ọlọ́jà Ọ̀ṣun ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ìjọba lórí ọ̀rọ̀ iná
0
Ó gba àwọn ọ̀dọ́ àsìkò yìí tó yan bọ́ọ̀lù gbígbá gẹ́gẹ́ bíi iṣẹ́ lámọ̀ràn.
0
Agbẹjọ́rò Bíṣọ́ọ̀bù ni Olúwọlá Oyèwọlé.
0
À-wí-ìgbọ́, àfọ̀-ọ̀-gbọ́ tí ń fi àjèjé ọwọ́ mumi.
1
Àjọ aṣọ́nà ní ọ̀pọ̀ èèyàn ló dèrò ọ̀run nínú ìjàmbá ọkọ̀ l'Ọ́yọ̀ọ́.
0
Àdúrà ká bímọ kó jọni, kì í s'àdùrà tẹkúwárápá lè gbà.
1
Àwọn olórin ilẹ̀ wá pọ̀ tó fakọyọ nilẹ̀ Adúláwò lọ́dún yìí
0
B'óyin bá pe lenu, a domi.
1
Àdán s'oríkodò; ó ń wòṣe ẹyẹ.
1
llésanmíjoyè lo.
1
Ó yọ̀ǹda ara rẹ̀ pé kí wọ́n fa òun lé àwọn ọlọ́pàá tó ń ṣèwádìí ọ̀ràn náà lọ́wọ́ m
0
Àtíkù àti Fálúsì sọ̀rọ̀ sókè nípa bí ìjọba Fálànà ṣé ti àkáúntì pa.
0
Èèyàn bí àparò layé ń fẹ́.
1
Ẹlego ẹdá ló ń runbẹ sìwájú (láwò)
1
Amọnà èsín ò mọnà mọ.
1
Ẹní a bá bá l'óde làá yàá kí.
1
Èèrà gbé'ra rẹ níyì, lóun aboníléjo pọn.
1
Apẹ̀rọ̀ níbi ọ̀rọ̀ gbé rọ̀, akígbe ogun ní ibi kólekóle
0
Àdúrà òbí ni kí ọmọ rẹ̀ ó ṣoríire.
0
Àtẹ́lẹwọ́ ẹni kì í tanni.
1
Àyẹ̀wò ìbátan tẹ̀gbọ́n-tàbúrò tàbí ti bàbá àti ọmọ lè súnmọ́ ara wọn.
0
Àjọṣepọ̀ tó wà láàárín èmi àti àwọn ọ̀rẹ́ mi kò ní jẹ́ ki ń tú àṣírí wọn.
0
B'á'ò r'eję, ó yę kí a rí omira.
1
Adelé ní Ọba Adérọ́jú wà lórí ìtẹ́ nígbà tí àwọn jàndùkú lù ú
0
Wọ́n ní ẹ̀jẹ̀ ń ya lára obìnrin náà nígbà tí ó di alẹ́.
0
Bí a bá ta ará ilé ẹni lọ́pọ̀, a kì í rí i rà lọ́wọ̀n-ọ́n mọ́.
1
Bọ́lárìnwá ló kọ́kọ́ jáde nígbà tí wọ́n fọn fèrè pé ìwà ọ̀daràn kan ti ń wáyé ní àdúgbò Arárọ̀mí.
0
Ta ni olórin tàkasúfèé tí Bọ̀bọ́ ń yó ìfẹ́ rẹ̀?
0
Aṣọ òkè jẹ́ aṣọ tó rẹwà.
0
Ẹgbẹ́ òṣèlú Alágbàdo ti ké sí àwọn ẹ̀ṣọ́ ààbò láti wádìí ọ̀rọ̀ yìí.
0
Ìròyìn sọ wí pé Adébísí fi oògùn orun sínú oúnjẹ fún àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin mẹ́rin.
0
Apàterogọdì ló dọkọ dúró dadínsinșin fókọ.
1
Àwọn òbí mi lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ náà.
0
Ìgbésẹ̀ ìjọba Èkó yìí jẹ́ èyí tí ó ń tẹ ẹ̀tọ́ àwọn ènìyàn lójú mọ́lẹ̀.
0
Bí a bá ń fe sínsín kù, làá f'owọ romú.
1
Ení kí ni rere, làá je rere.
1
A kì í wélẹ f'ádìe jẹ.
1
Ọ̀pọ̀ ènìyàn ni wọ́n gbà pé àìsàn kì í ṣe ọ̀rẹ́ fún ara.
0
Ní òwúrọ̀ ọjọ́ Ajé ni a gbọ́ pé èyí ṣẹlẹ̀.
0
Ṣọ́jà gún oníjà ọ̀rẹ́ rẹ̀ lẹ́yìn àti ní gbogbo ara títí tó fi ṣubú lulẹ̀.
0
Bí òyìnbó bá máa lọ lọ́gbà, a ba ọgbà jẹ́ .
1
A kì í bọ òrìṣà lójú ọ̀fọ́n-ọ̀n; bó bá dalẹ́ a máa tú pẹpẹ.
1
Agbẹjọ́rò Àfáà Babátúndé láwọn ṣetán láti yí ìdájọ padà.
0
B'éèyàn 'ò jỌba, yóó jẹbà.
1
Àwọn olólùfẹ́ gan-an ló máa sọ̀rọ̀ tí nńkan aburu bá ṣẹlẹ̀.
0
Ẹsín Ológìnní ò sí lọwọ Èkúté ilé.
1
Àìsàn kan ò lè kó ọgbọ̀n ikú lọ.
1
Agbọ̀ràndùn bí ìyá ò sí; ẹni tó ní baba ló tó ara-á ré.
1
Olórí ẹgbẹ́ àwọn amòfin ilẹ̀ Nàìjíríà gba iléeṣẹ́ ètò ìdájọ́ nímọ̀ràn.
0
Ẹkùn làna, a kì í rí ì fín.
1
A gbọ́ pé ọkùnrin tó ṣiṣẹ́ ibi náà ti sá lọ.
0
Ẹ ṣàánú wa, wọ́n ti fẹ́ pa wá tán - Àwọn ará ìlú figbe ta
0
Ìgbéyàwó tí Agúnbíadé ṣe ní oṣù mélòó sẹ́yìn ti forí sọ́npọ́n.
0
Àgbìgbò ló mórí ìyà wáyé; orí tó máa gbeni ò d rù pani.
1
Bomo ààyòò yó,ará tó kù ò jeun.
1
Ajá kì í gbó níbojì ẹkùn.
1
Àjà tí kò lọmọ nínú kì í jẹpè Òòșà.
1
Ní Olú-òjé ni ìròyìn sọ pé ọmọ obìnrin kan di àwátì nínú oṣù kẹrin.
0
Wọ́n ti fa àwọn ọmọ ilé kéwú Àlùmọ́njìrì méje jáde lábẹ́ Ilẹ̀pa tó wó lù wọ́n.
0
Bádéjọ sọ fún àwọn adarí pé kò yẹ kí àwọn máa gbé inú ìdè nítorí kò bójú mu.
0
A kì í bínú ààtàn ká dalẹ̀ sígbẹ̀ẹ́ .
1
A ń kì í, à ń sà á,o ní o ò mọ ẹni tó kú.
0
A kì í gbé ọmọ Ọbà fún ṣun.
1
Igbá-kejì olórí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tẹ̀lé ni Olóyè Ìkẹ́.
0
A kì í kánjú tu olú-ọrán; igba ẹ̀ ò tó-ó sebẹ̀.
1
Àgbàlagbà kì í sàsọsẹ, ọmọlúàbí 'ò yę kó sàsokóję.
1
Bí ìyàwó ọ̀lẹ́ bá dàgbà, olówó ni yó gbé e.
1
Ẹbọ jíjẹ kì í pa igún.
1
‘‘Mo dára, mo dára,’’ àìdára ní ń pẹ̀kun ẹ̀.
1
Bí ọmọdé bá ní aṣọ bí ìyá-a rẹ̀, kò ní èyí tí ìyá-a rẹ́- fi pọ̀n ọ́n.
1
Eșin ọtá eni kì í ga.
1
Ẹsẹ̀ rẹ̀ méjèèjì wà nílẹ̀ lásìkò tí wọ́n rí òkú rẹ̀.
0
Ẹlú yóó kùú; kò kú jẹ, ó ń lọ ó tún mú lẹbúlebú dání.
1
Alágbàtà ní ń sọ ọjà-á dọ̀wọ́n.
1
‘‘Kí ni Lágbájá lè ṣe?’’ Ìjà ní ń bẹ níbẹ̀?
1
Adìẹ́ yẹ̀gẹ̀; a ṣe bí ó ṣubú.
1
Bákan náà làwọn ọmọ ogun ilẹ̀ Iléṣà ti ṣàwárí ọ̀nà kan ti àwọn agbébọn ń gbà, láti fi wọ ilẹ̀ Ifẹ̀.
0
Àrán nìparí ọ̀ṣọ́.
1
Oníròyìn dúpẹ́ púpọ̀ lọ́wọ́ rẹ̀ fún àsìkò rẹ̀.
0
Ọ̀wọ́n gógó ọjà ti lé ọ̀pọ̀ okò-òwò wọlé.
0
Ọ̀gbẹ́ni Àjànàkú gbóríyìn fún aláṣẹ ìlú rẹ̀ fún akitiyan wọn.
0
Ìjọba sọ wí pé àwọn àyípadà tuntun yóò bẹ̀rẹ̀ ní ẹ̀ka ilé kíkọ́.
0
Bí a bá fi ọwọ́ ọ̀tún na ọmọ, à fi ọwọ́ òsì fà á mọ́ra.
1
Ọwọ́ tẹ àwọn ọ̀daràn márùn-ún.
0
Ẹ̀rọ sanwó lé ní àkókò tí ẹ̀rọ ilé ìfowópamọ́ yọnu.
0
Afurasí adigunjalè tó wa ọkọ̀ náà bẹ́ bọ́ọ́lẹ̀ lórí eré láti sá lọ.
0
Ẹ̀kọ́ tó yèkoro ṣe pàtàkì fún àwọn ọmọdé.
0
Àgùàlà ń bá oṣù rìn, wọ́n rò pé ajá-a rẹ̀ ni.
1
Dédé aago mẹ́fà ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ Àìkú, ọjọ́ kejìlá oṣù karùn-ún ọdún tí a wà yí ni ìṣẹ̀lẹ̀ kan ṣẹlẹ̀.
0
Bí a bá fa àgbò féégún,àfiokùn-un rẹ̀ sílẹ̀.
1
Adébipani kì í ṣọ̀rẹ́ ẹni.
1