Proverbs stringlengths 8 373 | Labels int64 0 1 |
|---|---|
Àwọn ọ̀dọ́ tí inú ń bí ọ̀hún ti dáná sun ilé méjì. | 0 |
Ikọ̀ ọmọ ogun ti béèrè fún ìrànlọ́wọ́ láti ọ̀dọ̀ ìlú mìíràn. | 0 |
Bí kò bá nídìí, Òșùșù-ọwọ kì í lé aítalẹ ọmọ onítúútú kiri ìyẹù. | 1 |
Araba ti bo lowo afefe. | 1 |
Kò jọ bí ẹni pé àwọn èèyàn mọ ewu tó wà níbí kí a máa gbé ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ kiri. | 0 |
Bí alẹ́ ẹni yó ti rí, òwúrọ̀ ẹni ni yó fi hàn. | 1 |
Ẹgbẹ́ onígbàálẹ̀ fá gbogbo ìbò tó pọ̀ jù fún ilé aṣòfin àgbà ní Ekiti. | 0 |
Èwwo ni tèkúté níbi p'ólógìnní ń fọmọ fọkọ? | 1 |
Ajóbíewé Àrẹ̀mú kì í mu sìgá. | 0 |
Orúkọ bàbá Àyìnlá Ọmọwúrà ni Gbogbolòwò. | 0 |
Eran oríso kì í jakùn, èyí tó jakùn, ara 'ẹ ló ń yọ lẹnu. | 1 |
Ìbọ̀wọ̀ fún àṣẹ àwọn adarí wa gbọ́dọ̀ jẹ́ pàtàkì sí wa. | 0 |
A ṣẹgi nígbó ẹgún, ẹgún ń sọ, àtẹgún àtigioko ta ló ni wọn? | 1 |
A kì í bánitan, kí á fani nítan ya. | 1 |
Ẹni tá ò fẹ, ààlọ 'ò ràn án. | 1 |
B'éégún bá ní igbọnsẹ ń gbọn òun,k'átọkùn má s'àfira, kí ówá'gbó súkútú, șúkútù, súkútú mú u wo, bí kó bá fẹ kómí aráorun. | 1 |
Dá-nǹkan-dá-nǹkan, tí kì í dáṣọ̀, tí kì í dẹ́wù. | 1 |
Ayé ò lọ́ràá: ọjọ́ a rí kéré ká jẹ kéré; ọjọ́ a rí wọ̀mù ká jẹ wọ̀mù; àgbà kì í ṣubú yẹ̀gẹ̀ kó da ti ikùn sílẹ̀; òun a bá jẹ ní ń bani lọ. | 1 |
Bí wọn kò bá ṣọ́ra, orúkọ lè jábọ́. | 0 |
Àwọn ológun ṣàlàyé ìdí tí wọ́n fi yọ̀nda àwọn tó jí àwọn akẹ́kọ̀ọ́. | 0 |
Ẹní fòókè; ó bẹ'jó lórí. | 1 |
Àwọn olóṣèlú kò ní wàhálà kankan pẹ̀lú rẹ̀. | 0 |
Adénúgà tún ní ilé-iṣẹ́ epo rọ̀bì. | 0 |
Àwọn agbófinró ti ti ibùdó ìbánisọ̀rọ̀ kan tí ó wà ní Ìkòròdú ní ìpínlẹ̀ Èkó. | 0 |
Pẹ̀lúmi pe àwọn ọ̀rọ̀ tí Bọ́lá sọ ní irọ́. | 0 |
Àwọn ọlọ́pàá sọ fún gbogbo wọn láti padà wá ní ọjọ́ mìíràn. | 0 |
Bíná bá ń jó n'ítòkú k'Ọbà má yọ,t'eni tódé la rí, teni tón bo a 'ò lè sọ. | 1 |
Ẹni tí 'ò ní baba kì í jìjà ẹbi. | 1 |
Adájọ́ gbọ́ ẹjọ́ igun méjèèjì. | 0 |
Àrà kí ni Ajítòní yóó dàá, ju kó kú. | 1 |
Òṣìyẹmí jíyìn iṣẹ́ àti akitiyan Iléeṣẹ́ rẹ̀ ní Aláùsá. | 0 |
Báyìí kọ layé șe wà rí. | 1 |
Bíná bá jó lóko, a bowo fọrun. | 1 |
Èèyàn mẹta wọlé, a fẹkan kù, eégún dé! | 1 |
Ẹ̀kọ́ inú eré orí-ìtàgé lè mú kí ọgbọ́n inú gbòòrò si. | 0 |
Ààrẹ wá bá àwọn ẹbí tí ọ̀fọ̀ ṣè kẹ́dùn lórí ìsẹ̀lẹ̀ burúkú ọ̀hún. | 0 |
Ẹse-èrò kì í dá nílée, Bù-ję-bù-dànù. | 1 |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga ń kérora owó ilé-ẹ̀kọ́ gọbọi. | 0 |
Àjàlá àti Àlào sáré tẹ̀lé ọkùnrin tó ń sálọ pẹ̀lú owó àti fóònù ẹni tí wọ́n jà lólè nígbà tí wọ́n ń ṣiṣẹ́. | 0 |
Ẹ jẹ́ ká wá ojú rere Ọlọ́run fún ìdàgbàsókè orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. | 0 |
Ọkùnrin tí wọ́n jù sí ẹ̀wọ̀n ni ó gbé egbòogi olóró. | 0 |
Àjọ elépo rọ̀bì sọ wí pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ epo rọ̀bì ní ìjọba Nàìjíríà ti tà tán. | 0 |
Abísọ́́lá pẹ̀lú àwọn tí ó bá ìdojúkọ pàdé nínú ètò ìforúkọsílẹ̀ fún nọ́ḿbà ìdánimọ̀. | 0 |
Àwọn ènìyàn méjì tí wọ́n ṣe iṣẹ́ abẹ fún náà sì jáde láyé. | 0 |
Arẹwà ní owó ìdáǹdè ìjínigbé ni agbébọn fi ń ra ohun ìjà olóró. | 0 |
Àgbà ìmàle kì í káṣọ kọ́rùn. | 1 |
Ẹwù l'Obìnrin ní, obìnrin 'ò nífèé (Kàyééfì Òwe yìí ni pé àgbàobìnrin kan ló pa á fún wa.) | 1 |
À-wín-ná-wó ò yẹni; à-gbà-bọ̀-ọ ṣòkòtò ò yẹ ọmọ èèyàn; bí kò fúnni lẹ́sẹ̀ a dòrògí; ohun ẹni ní ń yẹni. | 1 |
A kì í namọ tán kí a tún máa bèèrè asọ. | 1 |
·Egbe eni làá gúnyán ewùràá pè. | 1 |
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní ọ̀rọ̀ nípa ìgbésẹ̀ tí ìjọba Èkó gbé ya òun lẹ́nu. | 0 |
Ẹ̀gàn ò pé kóyin má dùn. | 1 |
N kò jẹ́ fọwọ́ kan nǹkan èèyàn bí wọ́n bá ní kí n máà fọwọ́ kàn án. | 0 |
Ìlú Ọ̀kínnì ni olóyè Àdìgún ń gbé. | 0 |
Ẹgẹ́ ò ṣákìí; ẹní bá bọ́ sábẹ́-ẹ rẹ́, a pa á kú pátá-pátá. | 1 |
Àwọn ológun láwọn ló dóòlà Ọba Èkó àti ìdílé rẹ̀ ṣáájú ìwọ́de. | 0 |
A kì í dédií lrókò s'aájú ẹlẹ́bọ. | 1 |
Ajá bu olówó rẹ̀ jẹ nígbà tí ó ń bá a ṣeré líle. | 0 |
Ẹní bá fẹ k'áraó rọ òun gbọdọ rọra. | 1 |
Iṣẹ́ ni ọ̀dọ́bìnrin yìí ń wá kiri. | 0 |
Ẹrọ nìrókò ń so; kì í so èle. | 1 |
Bí kò bá sí ohun tó ṣe ẹ̀ṣẹ́, ẹ̀ṣẹ́ kì í ṣẹ́ . | 1 |
Akú, n kò ní omitooro-o rẹ̀ ẹ́ lá; àìkú, nkò níí pè é rán níṣẹ́ . | 1 |
Àwòsùn-ùn, àwònù lẹkùn ń wẹyẹ òkè. | 1 |
A ṣì lè rí ọ̀nà àbáyọ sí àwọn ìṣòro wa bí ó bá tilẹ̀ fẹ́ le. | 0 |
Bi a bá sún kan ògiri; à á káwọ s'ókè ni. | 1 |
Ẹ̀gbọ́n ọmọdébìnrin náà ni Moyọ̀sọ́rẹ Gbóyèga. | 0 |
Ọ̀gá ọlọ́pàá ti fojú afurasí tó ṣekú pa àwọn tọkọtaya hànde. | 0 |
Afefe níí s'ewé-oko láíloláílo. | 1 |
Ẹlẹ́jọ́ kú sílé, aláròyé kú síta gbangba. | 1 |
Bówó bá dé má pe ẹnìkan lọ́lẹ. | 0 |
Dípò àwọn ohun tí àwọn kan ń sọ kiri fún àwọn oníròyìn. | 0 |
Láti kékeré ni ọmọ Balógun ti ń gbádùn iyì orúkọ bàbá rẹ̀. | 0 |
B'ójò ò rọ, tágbàdo 'ò gbó; ojuú takọ tabo ni yóó já a. | 1 |
Ẹní díre mọlé; kì í rí tòde gbà. | 1 |
A gbọ́ pé àwọn tó ń gbàtọ́jú náà ń bínú lórí ìwà tí àwọn dókítà Arò náà ń hù. | 0 |
Agbẹnusọ ọlọ́pàá sọ pé àwọn fura sí ikú ọkùnrin ọlọ́dẹ àdúgbò ọ̀hún. | 0 |
Ìtìjú ńlá gbáà ni pé àwọn kan ṣì ń fi dúdú pe funfun nínú ìjọba. | 0 |
A kì í dájọ́ orò ká yẹ̀ ẹ́ . | 1 |
Bí a kò bá tó baba ọmọọ́ ṣe, a kì í pe alákàrà. | 1 |
A kò lè rí Irúfẹ́ àwọn ènìyàn ńláńlá tí wọ́n ti lọ mọ́. | 0 |
Ajagunfẹ̀yìntì Mobọ́lájí di olóògbé. | 0 |
A kì í șòòșà l'ójú Ọfọn-ọn, bó délé a kó tię séwé. | 1 |
Àtẹ́lẹsẹ̀ ní ń jẹ̀gbin ọ̀nà. | 1 |
Àbíkẹ́yìn ló nìyá. | 1 |
Àgbéga ti dé bá ìlànà àgbékalẹ̀ ojú òpó ìdákọ́ńkọ́ àti ayélujára wa. | 0 |
Béèyàn bá ní òun mọ ọ wí; k'ó máa níran ẹni tó mọ o gbo. | 1 |
Ìròyìn sọ pé àwọn tí wọ́n lùgbàdì àrùn ń kú ní ìṣẹ́jú ìṣẹ́jú. | 0 |
Ọkọ̀ àjàgbé ejò kan sọ ìjánu rẹ̀ nù nílùú Ìsẹ́yìn. | 0 |
Ó ní òun lérò pé lábẹ́ ẹsẹ̀ òun ni ilẹ̀-rírì òun yóò ti lanu ni. | 0 |
Àárín gbùgbùn ìlú ni wọ́n fi ìpàdé àwọn ẹlẹ́gbẹ́jẹ̀gbẹ́ náà sí. | 0 |
Bí a ó jọpọlọ, kí a jẹ èyí tó lẹyin. | 1 |
Ọ̀nà àbáyọ yóò wà láìpẹ́ sí àjàkálẹ̀-àrùn. | 0 |
Àjọ ayánilówó àgbáyé ti sọ pé kí ìjọba Nàìjíríà yé san owó ìrànwọ́ orí epo rọ̀bì tipẹ́. | 0 |
Pàbo ni gbogbo ìgbìyànjú wa tún já sí lórí àti-gba béèlì ènìyàn wa. | 0 |
Bí ọmọ́ bá ti rí là ńṣe àna-a rẹ̀. | 1 |
Ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàmbá ilẹ̀ rírì ti fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ dúkìá ṣòfò. | 0 |
Bi a bá se náwó tó, leégún fii jó fún ni mo. | 1 |
Erù kì i bani kóri sá (kó) wonú. | 1 |
Àwọn akẹgbẹ́ wọn tó dá pé ń gbowó jù wọ́n lọ. | 0 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.