Proverbs stringlengths 8 373 | Labels int64 0 1 |
|---|---|
A kì í bá baba ta ifọ̀n tán ká tún ba ọmọ ta eṣinṣin kúrò. | 1 |
Ẹ báà lọ lọ lọ bí ọlọ, kí ẹ rè rè rè bii erè; ibi ẹ ti lọ lẹ ó fàbọsí. | 1 |
A pè ọ́ lọ́mọ erín-màgbọn ò ń yọ̀; ìwọ pàápàá ló mì í? | 1 |
Ọmọ Balógun sọ wí pé níṣe ni wọ́n máa ń pariwo orúkọ ìnagijẹ àwọn. | 0 |
Ewé ìgbá 'ò tó àkàsùú dì; igbá ńlá 'ò séé d'àwọn ká. | 1 |
Àwọn agbébọn dá ọkọ̀ tó ń gbé àwọn ẹlẹ́wọ̀n lọ́nà ní ìpínlẹ̀ Ògùn. | 0 |
Wọ́n gbé èyí tí wọ́n fẹ́ lò ní ìlú Súnmọ́mi sí Ẹlẹ́yẹlé. | 0 |
Gbọnyingbọnyin ni ťòkè, òkè náà gbọnyingbonyin. | 1 |
Ilé ìwòsàn ìjọba ti kéde àyẹ̀wò ọ̀fẹ́ fún àwọn aláboyún. | 0 |
Àjọ tí ó ń mójú tó ẹ̀tọ́ àwọn ọmọdé fún ìyá ọmọ náà ọ̀sẹ̀ kan. | 0 |
Àwọn ọlọ́pàá tètè dá ìpàdé àwọn jàǹdùkú dúró ní Ògùn. | 0 |
Bí a bá tàròwà ejò, a ó dánáa rẹ gbọọrọ. | 1 |
Àtètèsùn làtètèjí. | 1 |
B'ikà bá rojo,èké kọ ni yóó dá a. | 1 |
A kì í ti ojú ogun wẹ́fọ́n. | 1 |
Aṣọ tí a bá lára eégún, ti eégún ni. | 1 |
B'áa gúnyán nínú ewé, tí a rokà nínú èpo-ẹpà,eni tí yóo yòo yóó yòó. | 1 |
Báwo lo ṣe ṣẹlẹ̀ gan-an, ni ọ̀rọ̀ tí ó ń jáde ní ẹnu àwọn ọlọ́pàá agbègbè ibẹ̀. | 0 |
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú méjèèjì tahùn síra wọn lórí ọ̀rọ̀ fásitì ọ̀hún. | 0 |
Àwọn ènìyàn ńláńlá ti lọ ní ilẹ̀ Yorùbá. | 0 |
Ilé olórogún kì í ṣe ibi tó ní ìfọ̀kànbalẹ̀ rárá. | 0 |
Ebi ò pàJèṣà ó lóun ò jẹ̀kọ Ọ̀yọ́; ebí pa ọmọ Obòkun ó jẹ ori. | 1 |
Yóò dára bí a bá lè jáwọ́ níbi gbígbé ìròyìn tí kò dára káàkiri. | 0 |
Akíọdé sọ wí pé ilé ìgbé àwọn ọlọ́pàá jẹ́ èyí tí ó ti pẹ́. | 0 |
Àsìkò tí pátákó náà ń fì̀ nínú ìjì líle ọ̀hún ni Àṣàbí ya àwòrán rẹ̀. | 0 |
Aì í p'ára-oko magbọn-ọn hun. A ní “èyí tí ẹ ń wò nnì, òru nì mo hun ún." | 1 |
Ago mọ́kànlá alẹ́ ni ìṣẹ̀lẹ̀ ìpànìyàn yìí ṣẹlẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Kwárà. | 0 |
Àwọn ọkọ àti ìyàwó máa ń ní aáwọ̀. | 0 |
Ààrẹ Nàìjíríà tuntun fẹ́ bá àwọn ọ̀dọ́ sọ̀rọ̀. | 0 |
Bí Ọlọ́run ò ṣe ẹni ní baba,àfiìyànjú ṣe bí àgbà. | 1 |
Ẹní ș'ọpẹ oore-ànà, ọnà òmíràn ló ń șán sílẹ. | 1 |
Wọ́n fi ẹ̀yìn Ràúfù ti àgbá nínú oṣù kọkànlá. | 0 |
Àwọn Májẹ̀kóbàjẹ́ tó wà nídìí ìwọ́de ni kò jẹ́ kó dìjà. | 0 |
Ọkàn gbogbo ìlú ò balẹ̀ nígbà tí àwọn jàǹdùkú bẹ̀rẹ̀ sí í dà gbogbo àdúgbò láàmú. | 0 |
Àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú Onígbàálẹ̀ ti mú oṣù kẹrin fún ìdìbò abẹ́lé wọn. | 0 |
A-dùn-ún-se bí ohun ť'Olọrun F'ọwọ sí. A-sòróó-se bí ohun t'Olọrun 'ò fọwọ sí. | 1 |
Abiyamo s'owọkòtò namọ ę. | 1 |
Àpótí aláwọ inú níí gbé. | 1 |
Àjíbọ̀wábá là ń bá ilà àtẹ́lẹwọ́; a ò mọ ẹni tó kọ ọ́; àjíbọ̀wábá lowó àdásan; a ò mọ ẹni tó jẹ . | 1 |
Àwọn orin kìrìtẹ̀ẹ́nì ni Ayéfẹ́lẹ́ máa ń kọ. | 0 |
Àfi'bẹpẹ, ebi búrẹdì kì í pàgbẹ. | 1 |
Húmùání gbogbo kọ ló ń j'oyè alága. | 1 |
Àwọn ìrírí mi ní ọgbà ẹ̀wọ̀n kò sunwọ̀n rárá. | 0 |
Gbogbo èyí tí Gbádégẹṣin ń bá kiri yìí kò lè ràn án lọ́wọ́ rárá. | 0 |
Àwọn ènìyàn ò fọkàn sí èébú àwọn kan lórí ayélujára. | 0 |
B'ákúwárápá bá rí Òsínwín yóó gbà pé nnkan ju nnkan lọ. | 1 |
Kò sẹ́ni tó mọ ohun tí wọ́n fà papọ̀ tí sójà fi bínú fa ọ̀bẹ yọ. | 0 |
Ọ̀pọ̀ àwọn aládùúgbò ni wọ́n sáábà máa ń jókòó sórí tébùrù obìnrin náà. | 0 |
Bí a 'ò bá fẹbọ sàirú, èrù á gòkè, ohun gbogbo a dilọpọ ilọpo. | 1 |
B'éwúrẹ ò kú a ò leè fawọo rẹ se gángan.B'ágùntàn ò kú, a f'awọ 'ẹ sàdàmọ. | 1 |
A gbọ́ pé àwọn adigunjalè yìí máa ń jí ọkọ̀ gbé tẹrùtẹrù inú rẹ̀. | 0 |
Bàtà ò jẹ́ ká mọ agésẹ̀ òyìnbó; a ṣẹ́ aṣọ létí kò jẹ́ ká mọ ẹni tí ń faṣọ ìyà bora. | 1 |
Àwọn àkàndá ẹ̀dá ní bẹ́ẹ̀ ìwọ́de ń tẹ̀síwájú. | 0 |
Ẹlesin tó lóun ó mu omi kànànga, òun kọ ni yóó délé wí, apako.ẹșin rẹ ni yóó délé ròyìn. | 1 |
Bí a bá nì eégún baba eni yóó jòó, bí ò jó mọ; ijà ò sí níbe. | 1 |
Bí ọmọdé bá gun òkè àgbà, ó ń láti gbọ́n. | 1 |
Ẹní sin'bi-ọmọ ló lọmọ. | 1 |
Adébóyè rọ àwọn aráàlú níbi ètò ìsìn náà. | 0 |
‘‘Ìṣe ẹ̀ ni’’ ò jẹ́ ká mọ ikú àbíkú. | 1 |
Fákẹ́yẹ sọ wí pé òun jí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ rẹ̀ lẹ́yìn tí òun gbẹ̀mí rẹ̀ tán. | 0 |
Awọ fẹ́lẹ́ bonú ni kò jẹ́ ka rí kùn òṣìkà. | 0 |
Ìjọba ìbílẹ̀ Orídádé béèrè fún ààbò láti ọ̀dọ̀ ìjọba. | 0 |
‘‘Bùn mi níṣu kan’’ kì í ṣáájú ‘‘Ẹ kú oko òo.’’ | 1 |
A-dá-má-lè-ṣe àdàbà tí ń dún bẹ̀m̀bẹ̀. | 1 |
Ará ìbàdàn kì í jẹ wọn ó yìn òun. Bí wọn ló yá a, a ní 'tóun ya Lábo, tóun tún ya Elékùró. | 1 |
Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá láwọn yóò fojú Fákẹ́yẹ ba ilé ẹjọ́ ní gbàrà tí ìwádìí àwọn bá parí. | 0 |
Ọlọ́pàá olóògbé náà kàn yìnbọn sókè láti ṣẹ̀rù ba àwọn tó ń ṣe fà-n-fà ni. | 0 |
Ebi ìyà, ó yá ju ayo lyà. | 1 |
Àjàdí dá àpá sí ìyàwó rẹ̀ lára nígbà tí wọ́n ń jà. | 0 |
A kì í pé kí ọmọdé má fẹ ehín gan-gan-ran bó bá tù ú; ètè ni kò rí fi bò ó. | 1 |
Ara ẹ̀ lara ẹ̀: ṣòkòtò ọlọ́pàá. | 1 |
Àjọjẹ ò dùn bí ẹnìkan ò ní; bí a bá ní là ń ṣe àjọjẹ. | 1 |
Wọ́n rí òkú ọ̀kan nínú àwọn tí wọ́n pa nílé ìwòsàn Ìgandò. | 0 |
A bá a kẹ́dùn kí a tó máa lọ ilé. | 0 |
Àwọn gbajúgbajà òṣèrè kan rí ogun ilé-ẹjọ́ nítorí ìwà ìbàjẹ́ tí wọ́n hù. | 0 |
Ayé ń retí ẹl yà; níbo ni wọ́n fi ti Olúwa sí? | 1 |
B'Ógèdègédé wọjà, eyẹkẹyẹ kì í ké. | 1 |
Yóò kàn tún máa dojúrú sí i ni. | 0 |
Àwọn èjìrẹ́ ń ṣe eré líle. | 0 |
Eléjo sa èyí tó dùn rò. | 1 |
Àrí-ì-gbọdọ̀-wí, baálé ilé yọkun lémú. | 1 |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fásitì Èkó ń ṣe ìwọ́de. | 0 |
Báwo ni ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣe jẹ́ gan? | 0 |
Baálẹ̀ ọkọ ìlú kú ní àná. | 0 |
Adékọ́lá wòye pé kìí ṣe Tinubu nìkan ló jẹ̀bi irú ọ̀rọ̀ yìí. | 0 |
B'éwé bá pẹ lára osẹ, ọsẹ níí dà. | 1 |
Wọ́n ti mú àwọn òbí ọmọ náà kúrò ní ilé tí wọ́n ń gbé. | 0 |
Àjọṣe tó dán mọ́rán wà láàárín orílẹ̀-èdè méjèèjì. | 0 |
A kì í dá ẹrù ikùn pa orí. | 1 |
Gogo-òwú ló ń jèrè òwú. | 1 |
Àgbà tí 'ò kẹhun sọrọ yóó kẹtan sáré. | 1 |
Eegun àjànàkú: ó há ìkokò lẹ́nu. | 1 |
Bí mo bá jí ma rorín kíjeyínjeyín máa sá fún mi. | 0 |
Afurasí kú sí àhámọ́ ọgbà ẹ̀wọ̀n ní Ìlọrin. | 0 |
Àjó-tawó-tasę ni ti tanwíjí. | 1 |
BBC Yorùbá kàn sí agbẹnusọ Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórí ìṣẹ̀lẹ̀ náà. | 0 |
Bí ọ̀pọ̀ èèyàn-án bá kúrò lẹ́gbẹ́, ọ̀pọ̀ a dáni lára yá. | 1 |
Àwọn èèyàn á máa fi mí ṣe yẹ̀yẹ́ tí mo bá fi lè kọjá láàárín wọn. | 0 |
Àdàbí ò p'ejò, à fì kóńdó. | 1 |
Ana tó rojú; ọmọ 'ẹ ní yóó gbà. | 1 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.