Proverbs stringlengths 8 373 | Labels int64 0 1 |
|---|---|
Àbá kì í di òtítọ́; ojo ni kì í jẹ́ ká dá a. | 1 |
Edun nii s'ọmọ oniyán, Òwe níi ș'ọmọ Ọlọbẹ. | 1 |
Epo ló ni jàngo, òwú ló ní fitílà. | 1 |
A kì í kórira ọ̀fọ́n-ọ̀n ká finá bọ ahéré. | 1 |
Bíseé n se odo (omode) láseejú,kó lo sígbó erin.B'ó bá perin;a á, ise re yóó bùse. | 1 |
Bí a bá ń b'ọmọdé jẹ'su l'óko, ìgànmùngánmún imú eni níí maáwò. | 1 |
Bàbá rẹ̀ máa ń fun ní ìmọ̀ràn pé ó gbọdọ̀ ṣe akitiyan láti gbé orúkọ ìdílé ga | 0 |
Dídé ló dé gbèsè Àbíjọ; ó yan gúgúrú ó kunlé, ó pọnmi tà ó dígbèsè. | 1 |
A sọ ọmọ ní Ṣódé, ó lọ síbi ó dé; a sọ ọmọ ní Ṣóbọ̀, ó lọ sájò ó bọ; a wá sọ ọmọ ní Ṣórìnlọ, ó lọ sájò kò dé mọ̀, à ń sọ̀. Ta ni kò mọ̀ pé ilé lọmọ-ọ́ ti mú orúkọ ànù lọ? | 1 |
Bí wọn yóò ṣe kojú ìṣẹ̀lẹ̀ pàjáwìrì yóò wà nínú ọ̀rọ̀ ìpàdé wọn. | 0 |
Àwọn kan lára àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ lérò pé ó ń dá àpárá. | 0 |
Bí a bá rí òkú ìkà nílẹ̀, tí a fi ẹsẹ̀ ta á; ìkà-á di méji. | 1 |
Bí ilé ń jó, bí olè ń jà, ẹni ebi ń pa yó máa wí. | 1 |
Eșinșin 'ò lárẹmọ, àșórín 'ò lólùkù. | 1 |
Àtẹ́lẹwọ́ ẹni kì í tanni. | 1 |
Bíjó àjùmọjo bá d'ijóó 'máa jó lọ, mò ń wẹyìn rẹ', kí a fura. | 1 |
Ẹsan 'ò gbóògùn, tọjú ìwà rẹ. | 1 |
Ọ̀nà ìgbàwáṣẹ́ yìí ló ti bá ara rẹ̀ nínú ọ̀gbun àwọn ajínigbé. | 0 |
Àtíkù pe owó tí ìjọba fẹ́ fi ṣe ọ̀nà ní Bílíọ̀nù mẹ́jọ Táyọ̀ pè é ní Bílíọ̀nù mẹ́rin. | 0 |
Àìsí owó là ńtìlẹ̀kùn mọ́ ọ̀ọ́dúnrún; kí ni irínwó baba ìgbiwó tó-ó ṣe? | 1 |
Bí àjànàkú ò bá gbẹ́kẹ̀lé fùrọ̀, kì í mi òdù àgbọn. | 1 |
Ìjà tó ń lọ lọ́wọ́ ni láàárin ikọ̀ ológun àti ikọ̀ afarajológun. | 0 |
Àròyé lórí àwọn tí ọkọ̀ gbá ní títì márosẹ̀ ṣì ń gba ìtọ́jú ní ilé ìwòsàn. | 0 |
Awọ ẹlẹ́dẹ̀ ò ṣéé ṣe gbẹ̀du. | 1 |
Etí méjì; ahọn kan, ò lásán, kí a bàà lè yára gbó; lọra fèsì ni. | 1 |
Alángbá 'ò (bá wọn) șákę, kò (bá wọn) họkùn, ó lé tente l'áruru aláruru. | 1 |
Alákàtànpó ṣe b'ọbọ ò lọ́gbọ̀n nínú; béè ọgbọ́n inú obo pẹ́gbàágbèje. | 1 |
Àwọn mọ̀lẹ́bí míì àtàwọn ará àdúgbò náà bá ikọ̀ ìròyìn wa sọ̀rọ̀. | 0 |
Orin kíkọ rọ Àyìnlá Ọmọwúrà lọ́rùn púpọ̀. | 0 |
Bí kìniún bá bú ramúramú nígbó,níjù,a ní kòs'ẹni òun páyàlókè-eèpe,àfi àferìn làkátabú, a tún fèèyàn abìdí yàn-án-yàn án. | 1 |
Atowo eni d'owọ eni ladìę fi dÓtù-lfę. | 1 |
Ẹ̀míọlá sọ pé àkókò rèé fún ẹ̀yà àwọn láti sọ fágbàáyé pé àwọn pọ̀. | 0 |
Ẹni ló ń muni mọ'ni, èèyàn ló ń múníi mọnìyàn, ìyáàmi ló mú mi mọ bàbáà mi. | 1 |
Bí àlááfíà yóò ṣe wà láàrin ìlú ni Ooni bá lọ sọ́dọ̀ Ààrẹ. | 0 |
Èmi àti ọ̀rẹ́ mi kan gba iṣẹ́ oko ríro ní agbègbè Ọ̀nà Ìràwọ̀. | 0 |
Àwọn aláṣẹ ilé ìtura fi ìṣẹ̀lẹ̀ yìí tó àwọn ọlọ́pàá létí. | 0 |
Èéfín nìwà; kò ṣé-é bò mọ́ra. | 1 |
Bí àjànàkú jẹ tí kò yó, ìgbẹ́ lojú ó tì. | 1 |
Asínwín ní òun ó ti iná bọlé; wọ́n ní kó má ti iná bọlé; ó ní òun ó sáà ti iná bọlé; wọ́n ní bó bá tiná bọlé àwọn ó sọ ọ́ si; ó ní ìyẹn kẹ̀ ìkan. | 1 |
Bàlúù ogun orílẹ̀-èdè wa kan ti já lójú ìjà pẹ̀lú àwọn jàndùkú. | 0 |
Láwàní sọ wí pé ìtàn tí kò dára ni ìjọba ń kọ sílẹ̀ fún ara rẹ̀. | 0 |
Àyẹ̀wò fún mọ̀lẹ́bí tí àyẹ̀wò ìbátan wọn bára mu. | 0 |
Àlùfáà dáná sun ilé ìyàwó rẹ̀ tó kọ̀ láti kírun pẹ̀lú rẹ̀ l'Ékìtì. | 0 |
Ajóbíewé Àrẹ̀mú kì í kó obìnrin. | 0 |
Àwọn Mùsùlùmí kò ṣe hùwà pẹ̀lú ìwé tí wọ́n gbàgbọ́ nínú rẹ̀. | 0 |
Bí òtútù ńpa ìwọ̀fà wọn a ní ó kó ìṣe-e rẹ̀ dé; bí ó ń pa olówó wọn a ní kó rọ́jú kó ata sẹ́nu. | 1 |
Àkẹ́bàjẹ́, ọmọ àgan-án-dáríjọ-bí. | 1 |
A-rọ́ba-má-sàá pàdé a-rọ́ba-má-yà; pẹ́kí ko pẹ́kí. | 1 |
Bí ná 'ò bá tán l'áșọ; ejẹ o leè tán léèkánná. | 1 |
Epọn tó bá sàn sílẹ làá ta ní kókó. | 1 |
Bí a ò r'ówó rẹrú, à sọ adie (ajá) lórúkọ. | 1 |
Bàbá Àjàyí nígbàgbọ́ pé ikú ọmọ òun kì í ṣe láti ọwọ́ Ọlọ́run. | 0 |
Àwọn darandaran ń da àwọn àdúgbò kan láàmú. | 0 |
Bí òfé ti ń fò la ti ń mọ̀ ọ́ lákọ ẹyẹ. | 1 |
Ejọ aja tó ja kọ, enì tó so ó nì ò so ó re. Ẹni tó so ó sì só o re,okùn tó fī so ó ni ò yi, okùn tó fi so ó yì, orúkọ ajá lò ń ro ajálajá fi ń já nígbà gbogbo. | 1 |
A tí mú Ọlọ́páà to f'ọ̀nà ẹ̀bùrú gba owó ẹ̀yìn lọ́wọ́ awakọ̀. | 0 |
Bi terin tefọn-yóó kùú, wọn a làwo lóri șasa-rașa. | 1 |
Ọ̀nà tó wọ inú ìlú Ayédáadé pọ̀. | 0 |
Àwọn jàǹdùkú agbébọn ń jí àwọn ènìyàn gbé lọ́sàn-án gangan. | 0 |
Àwọn ọlọ́pàá mẹ́ta ni wọ́n jẹ́ ẹ̀ṣọ́ fún gbajúmọ̀ olórin kan ní ìlú Kánò. | 0 |
Lẹ́yìn èyí ni wọn yóò mú ọkùnrin ọ̀hún lọ sí ọgbà àtúnṣe | 0 |
A kò ní ṣe ìwádìí kankan lórí òṣìṣẹ́ tí wọ́n ló gba ẹ̀mí ara rẹ̀. | 0 |
Dámilọ́lá ti ń ṣe aya lọ́ọ̀dẹ̀ Òkìkíọlá láti ọjọ́ mẹ́ta. | 0 |
Bíkán bá ń mu orù, kí akèrèngbè má sàfira. | 1 |
Àwọn ẹbí Tósìn wí pé ẹ̀rù ń bà wọ́n lóri ìlera ọmọ wọn. | 0 |
Ọmọ ìkókó kò lè jẹ oúnjẹ òkèlè. | 0 |
Kàkà kí Lóńgẹ́ tọrọ àforíjì nílé ẹjọ́ níṣe ló ń pariwo. | 0 |
B'órí pẹ nílẹ, a dire. | 1 |
Ẹ̀lukú tí kò ní èlè lẹgbẹ́-ẹ rẹ̀ ń ṣá pa. | 1 |
Ó sọ wí pé ọ̀rẹ́kùnrin òun sọ pé ẹ̀gbọ́n òun ń wá èèyàn tí yóò bá a ṣiṣẹ́ ní Ìtaọlá. | 0 |
Ìwádìí ìjìnlẹ̀ ti bẹ̀rẹ̀ lórí irúfẹ́ okò-òwò táwọn kọ̀lọ̀rànsí ẹ̀dá kan ń ṣe. | 0 |
Aláǹgbá kì í lérí àti pa ejò. | 1 |
A kì í ka ilé òrìṣà kún ìlú. | 1 |
Irúfẹ́ ìwà yìí ti wáyé lásìkò tí Gómìnà ṣe ìyànsípò lẹ́ka ètò ìdájọ́. | 0 |
Ẹnu tó bá ti gba dòdò, ko leè gba òdodo. | 1 |
Kò sí nǹkankan tó ń ṣe ọ̀pọ̀ àwọn tí wọ́n dá padà sílé. | 0 |
Àwọn kan sọ̀rọ̀ burúkú sí Dámilọ́lá. | 0 |
Àsúnmọ́ dẹ̀tẹ́; èèyàn gbókèèrè níyì. | 1 |
Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ sọ wí pé owó òṣìṣẹ́ táwọn ń béèrè fún ló ṣe kókó. | 0 |
Àkèré niì bá j'ọba Odò, ayọ àyọpọrọ ni ò jẹ. | 1 |
À rí ìgbọdọwí; ipin lójú ẹlẹmu. | 1 |
Adarí ìpínlẹ̀ tí bọwọ́lu àbádòfin ètò ìsúná ọdún yìí | 0 |
Afiniṣe kì í jẹ́ ká fòun ṣe. | 1 |
Bí iná bá jóni, tó jó ọmọ ẹni, tara ẹni là ń kọ́ gbọ̀n. | 1 |
Awoníní kọjá àlùkùráni. | 1 |
Wọ́n yóò fi bàlúù gbé wọn láti Ìjàòdọlà sí ìlú Òmìnira. | 0 |
Adámú ò lè wà nílé ká má gbọdọ̀ ṣe han-han. | 1 |
Àìgbọ́ra-ẹni-yé wà lára ohun tí ó máa ń bí ìjà. | 0 |
Àṣàdànù, àṣàdànù lọmọdé ń ṣa òkúta ìta baálẹ̀. | 1 |
Ìbéèrè tó wà nílẹ̀ ni wí pé ṣé wọ́n máa ṣe é. | 0 |
Àwọn ènìyàn tí wọ́n kó àrùn ní ìlú Ìràwé ju ti àwọn ìlú yòókù lọ. | 0 |
‘‘A ò mọ̀yí Ọlọ́run yó ṣe’’ kò jẹ́ ká bínú kú. | 1 |
Bí owó bá pọ̀ ọ̀rẹ́ àtèrò a pọ̀; bówó bá tán gbogbo wọn a wábi gbà lọ. | 1 |
Àwọn òǹkọ̀wé sọ wí pé Iba ni àwọn yóò fi jẹ olórí tuntun. | 0 |
B'Ólúwá Bá fe kí nnkan ó fò, yóó fún un níyèé. | 1 |
B'ójú bá kojú ààlà a tọ nídìí ìgbá. | 1 |
Adarí ẹgbẹ́ jàǹdùkú Ẹlẹ́sìn Òkèèrè jáde láyé. | 0 |
Anumọ kì í nulẹ, ẹnu Anumọ lọwọ́ Anumọ ń lọ. | 1 |
Ààrẹ tẹ́wọ́ gba àbájáde ìwádìí ọlọ́pàá pé wọ́n fẹ́ yọ Dayọ̀ nípò. | 0 |
Àkọ́kọ́ ní í ṣe pẹ̀lú ìwà àmọ̀ọ́mọ̀ ṣe. | 0 |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.