text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
Ire. Ire lojú owó ń rí | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ltlt oooo amin ase oo aku odun rt ẹ káàárọ̀ o a kú ọjọ́ òmìnira o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìwọ̀n oníwọ̀n là ì í mọ̀; a máa ń mọ ìwọ̀n ẹni. #EsinOro #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
a ó gbo ewé ifin sínú igbá a ó fi ẹfun sí í obìnrin olóyún á máa mu ún ń wákàtí wákàtí | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ayé alágbádá la wà, tùbíǹnùbí l'ó yẹ a fi yanjú ọ̀ràn ilẹ̀ yìí. Kí gbogbo àwọn t'ọ́ràn kàn ó jókòó kóníkálukú ó múmọ̀ràn wá. @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Orí bá mi ṣe tèmi k'ógún, kí ó gún gẹ́gẹ́. Oríì mi Ẹlẹ́dàá mi gbè mí, máà jẹ́ kí ewé ńláà mi ó rún wẹ́wẹ́. Orí máà dà mi padà sẹ́yìn, ìtẹ̀síwájú lọ̀pá ìṣẹ́gun, nítorí agbeni l'orí ẹni, A-kọ̀-máà-gbòṣìkà Olódùmarè f'oyin s'áyéè mi, kí o bù kún ireè mi. #iwure | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọmọ adú Marc Hannah l'ó ṣe ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ayàwòrán tí a mọ̀ sí 3D. #BHM | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kíni ìtumọ̀ irun wa? #AwaLaNiIrun | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ta ló fẹ́ bá'lúwarẹ̀ gún'yán nínú òtútù ọ̀rẹ́ mi :) | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
“@user: @user beeni Kosi iro nibe.”àwa la ni í, tiwa n tiwa. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Bẹ́ẹ̀ ni, ọpọlọ àwa èèyàn kò dọ́gba, fún ìdí èyí sùúrù ló gbà. Mo dúpẹ́ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
obo lowo yin eyin oniranu burukuibo lo ti so pe | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ifá bá mi fárí-ì mi o! Ọ̀rúnmìlà sọ mí d'ọlọ́là kí n là. Ìtẹ̀síwájú l'ọ̀pá ìṣẹ́gun, bẹ́ẹ̀ni yó rí fún mi lónìí tí í ṣ'ọjọ́ Ìṣẹ́gun. #OjoOse | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àlàpà tó dẹnu ílẹ̀ ẹran oríṣi ní í fi bẹ̀ ṣe lé tára bá bájẹ́ talára ní í dà bí ọ̀rọ̀ àgbà | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
yoòbá ní gbàgbọ́ pé ẹ̀mí elédùmarè wà ńnú ẹni kẹ́ni tí í ba ṣe nǹkan àràmàndà tí wọn kò rí rí | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìtan-an Mama Drama náà tu ni lára, ó jẹ́ àrà ọ̀tọ̀. Ó tayọ. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
CAN: Ìbànújẹ́ ńlá ni iku ọ̀mọ̀wé Musa Asake jẹ https://t.co/8C5NkuKi7F https://t.co/LmWlQEtaMC | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: TAKE IT #SIckleCellAwareness in #Yoruba Osu kesan, osu #september je osu pataki fun wa gegebi awujo. Idi ni pe, a maa n fi… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user tanmọdé sóko/tanmọlọóko; tanmọóko; tan ọmọdé lọ sí oko #idahun #yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mọ́kàndílọ́gbọ̀n nínú ọgọrun | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ àgbà sì ni pẹ̀lú gbìyànjú ẹ̀ wò náà | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: @user Please tell me de phrase: #Bringbackourgirls #InYoruba, i will appreciate that, thank u,""""Ẹ dá àwọn ọmọbìnrin wa padà | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ohun tó bàjẹ́ àti irú ibi tí Ọwá ni gbogbo ibi ni ti ìpílẹ̀ | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ọmọge aláìlójútì. Ilé sílé sílé lọ́ ti ń ká wọn láṣọ s'ókè. Ẹ ṣọ́ ṣe #Ife #AyajoOlolufe | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Saturn ló ni Saturday, oòrùn ni à ń bọ lọ́jọ́ Sunday. Àwọn orúkọ ọjọ́ wọ̀nyí ti yí padà àbí ó sì wà bẹ́ẹ̀? #Kojoda #daysoftheweek #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀rúnmìlà ni ajẹ́rìí ọ̀rọ̀ mímọ́ Ọlọ́run, gẹ́gẹ́ bí Adéwálé Mùọ́mọ́dù àti Jésù ṣe jẹ́ ajẹ́rìí ẹ̀sìn ìgbàlódé lonígbà ń lò. #YorubaMoOlorun | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: @user Nje eti wo cinima 'Omo Gba jensimi' ri?"""" N ò rò bẹ́ẹ̀, ta ní ṣe é? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Hinpele o gbogbo Ujèsà, Oni a San wa o. Obòkun a gbè wa o. Oruko mi ni Olaniyi omo baba Oluwakuyide lati ilu Ulesa. 😄 #TweetinYoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ṣé o mọ̀ pé ilẹ̀ tí a fún àwọn ẹrú agbòmìnira láti #Sierraleone ni #SaroTown tí ó wà ní #LagosIsland? #DidYouKnow #Yorùbá #Repatriation | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
♥ Àwọn Yorùbá ní ìlànà tí wọ́n ń gbà wí ire sínú ayé wọn tí ohun rere fi ń bá wọn gbé. Ìlànà yìí ni à ń pe ní Ì-WÍ-IRE. #AsaIwure | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#iroyin, #yoruba, SWAN Osun kede ojo idibo won: Tolulope Emmanuel, Osogbo Egbe akoroyin ere… https://t.co/qM9aDimhHd | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Bẹ́ẹ̀ ni, department of African languages lẹ́yìn Philosophy. Ó yẹ kí a mọra nìyẹn o. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ṣé k'á má w'ọṣọ gidi mọ́ ni... #EndSARS #EndSWATNow #EndPoliceBrutality #EndInsecurityNow #EndBadGovernanceinNIGERIA https://t.co/RFmEqmx8yw | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
won pe egungun to leran lara kpomo gbera ask your friend the meaning | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Njẹ́ ọ̀rọ̀ wa ni Afirika lè lójútùú láí-láí bí? Ogun níwá, rògbòdìyàn lẹ́hìn. Orígun mẹ́rẹ̀rin ilẹ̀ adúláwọ̀ wa polúkúrúmusu. Èé ṣe? | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bẹ́ẹ̀, ó sì lè ṣe ọmọ ogun lábẹ́ olórí ogun rẹ̀. Gẹ́gẹ́ bíi ọmọ ogun tí a bí ní ìbí ọmọ, ẹrú tó gba òmìnira yìí ní láti fún olórí ogun rẹ̀ ní ẹrú kan tàbí méjì tí wọ́n mú lójú ogun, ní gbogbo ìgbà tí ó bá dé láti ogun. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ta ń mọ̀ ọ́ o? #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kò sí ọ̀rọ̀ tí a lè pè nírọ́ nínú ọ̀rọ̀ onígẹ̀gẹ̀ tí ó bá ní gẹ̀gẹ̀ òun bí ó ti tóbi tó yẹn bẹ́ẹ̀ ni ó ń ta òun tí ó ń ro òun ó yẹ kí a gbà á gbọ́ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fìlà ni abetí-ajá àti àrámọ́rí,___ ni bálá àti ṣọọrọ? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Osun..... Ire wo le de... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""@user: Ṣé ẹ ti délé àbí ọ̀nà lẹwà? Èmí ti wà nílé láyọ̀ :)"""""""" ope ni fun oluwa. E ku ogun aja bo ti t'oni . | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìwo náà lánfààní láti sọ ìtàn yorùbá fún wa bí ti ṣe ṣe ẹ jẹ́ a kọ́ra wa lọ́gbọ́n ìmọ̀ èdè àṣà oòduà | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user ẹ ní kí wọn dá ọkùnrin ni sílẹ̀, ẹ ṣe ìwádìí fínnífínní, kí ẹ rí òkodoro ọ̀rọ̀. Kò m'ọwọ́ kò m'ẹsẹ̀ nínú ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn án. Àbá ni kì í ṣe àṣẹ... À ń jẹ èkuru kí ó tán, ẹ tún ń gbọn ọwọ́ 'ẹ̀ s'áwo. #FreeWale #EndPoliceBrutality https://t.co/NbDeA9K4Hg | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: 12. Ṣe ògbùfọ gbólóhùn yìí sí èdè #Yoruba : """"""""The electric pole gave him a shock and he fell headlong """""""" #Ibeere #Yoruba h… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òwú ò sí ní'lé, abẹ́rẹ́ wọ́n lọ́jà"""" ni'gbe ahun t'áṣọ ọrùn rẹ̀ fi ń di àkísà. #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré ńlá. . Mi ò ní òye ìdí tí eré ńla yìí fi ní àgbéyèwò tí ó kéré tó bayi.Eré náà dùn tí mo fi gbogbo ọkàn mi síi gẹ́gẹ́ bí ọmọ akẹ́kọ̀ ilé ìwòsàn.. . Ise takuntakun and òsùbà fún àwọn adarí àti olùgbéjáde Eré náà. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: """"""""@user Ofin: ewon odun mewa ni fun enikeni ti o ba lowo si igbeyawo awon onikan ara kan na - Are Jonathan... http://t.… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ohun kan tí ó fi ní jẹ́ kí ó rí bẹ́ẹ̀ ni bí a bá mú èdè wa ní gbòógì, kí a máa mú u lò lójoojúmọ́. #EdeAbinibi #Yoruba #IMLD17 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Òwe yìí báwa wí gidi-gidi ní àkókò tí a wà yí o. Ẹ ṣeun gan-an ni! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
a pọ̀ tí a sùn lálẹ́ àná ojú orun ni àwọn kan gbà dé ojú ikú àmọ́ àwa ò gba ojú orun wọ sàárè bàbá a dúpẹ́ pé o pa wá mọ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
táwọn nǹkan àjèjì bá ti ń yọ sí wa lójú kíá ka gba ilé ojú lọ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọ̀rọ̀ náà ń sọ pé obìrin aya ọkùnrin ti wà nílé náà kò sí ohun kan ìyàwóilé pẹ̀lú àlè ìta torípé obìrin ilé ló lọkọ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Gbogbo ojo l'o ye ko je #Tweetinyoruba O se dandan ki a gbe ede ati asa wa laaruge | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ojúmọ́ tí ó mọ́ wa lónìí ojúmọ́ ire ni kó jẹ́... Ire gbogbo k'ó máa wá wa wá... 🙏🏽 https://t.co/kzweBYOi8Q | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
9. Ring worm ni sòbìá, cancer ni jẹjẹrẹ, kíni measles? #Ibeere #Yoruba #learnyoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
episode pàtàkì orúkọ nílẹ̀ yorùbá | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ẹyìn tí yóò di epo, yóò tọ́ iná wò. / A palm nut that wants to become palm oil would have a taste of fire. [There's a… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àìṣedéédé àìdọ́gba ti melodrámà àti àwọn ẹ̀rù ti ogun abẹ́lé | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ó tún mú mi rántí òwe Yoòbá, tó ní """"""""orí yeye ní ńmògún, t'àìṣẹ̀ ló pọ̀"""""""". #yoruba #proverb #PlaneCrash #LagosState | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ojú la rí a ò rí inú aṣebí ọgbọ́n àti gúnwà sórí àga ìṣàkóso okòwò wa ni èèbó ń bá bọ̀ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹkú ìdájí o. Ìdájí atẹ́gùn tútù. Tútù tútù lẹ ó bá pàdé lónìí ẹ ò ní rí gbígbóná o. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kì í ṣe torí pé ó dùn jù. https://t.co/ghjX8a1MmY | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ire ni ti wa. Ire kàbìtì | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user @user Ojumo to mo wa leni, ojumo ayo ni o je! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹkáàárọ̀ o ẹ sì kú afẹ́rẹ́ òní ò ní jọ àná èmi wíi alèwílèṣe á ṣe bẹ́ẹ̀ a á ṣẹ bẹ́ẹ̀ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Èdè wa oni pare la gbara eleduwa nitori ise takun takun ti awon baba wa bi Faleti, Ishola, etc ti se… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ewoo e se jare tabi eyin naa nife sii?""""""""@user: Aa gba ibi ire o,lol RT""""""""@user: Lotito ni oro awon agba to ni ebi kii wonu ki | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Lateteji. owo nije mo ba o tan, osi ni je, talo mo o ri. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user A jíire, ara á le koko | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ṣebí abẹ́ ìṣàkóso Àfọ̀njá ni Ìlọrin (Aréwá Ọ̀yọ́) wà nígbàa ni, èyí ò tó o, ó fẹ́ gun orí àpèré ń tipátipá. #ItanFulani #Darandaran | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Orí mi kà á gbé s'ógun, àjàyè ni mo jà | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Egbirin ote. Iwoyi laro ti wan se mo wipe oye ki omo Karo o jire fi owo so wo po. Wan ti ri awon mekunu ge ge bi opon ayo. #YorubaRoNu! https://t.co/PYviiQ267O | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
yorùbá sábà máa ń ṣe é ládùúà pé mi ò ní kú mi ò ní rùn ọmọ kú oótùoòjíire kí ní ìtumọ̀ rùn nínúu gbólóhùn yìí | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn wo ni a máa ń pè ní """"""""apàlọ́ pa títà?"""""""" #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
wọ́n kó ẹjọ́ lọ sí ọ̀run lọ́dọ̀ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ìbàjẹ́ ọjọ́ kan kì í tán lógún ọdún. / An indiscretion of one day, does not get forgotten in twenty years. [Acting in … | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ṣe o dá ojúbọ Ṣàngó mọ̀? #worldsangofestival #Sango #Oyo | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ilẹ̀ ti fa omi mu. Ooru á wá gboró sí báyìí | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àgbá òfìfo ló ńpariwo èyí tó lómi nínú kì í dún its empty vessels that are noisy those filled with water are not | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
aaaah aunty temi nitori olohun ewo lebo oran | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ise gbogbo wa ni,iran lowo ti a ri gba ni a lo lati ran awon eniyan l''owo. Ki ipologo asa ile wa wa ku RT @user… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìlàìsọdá ọ̀hún ti fẹ́rẹ̀ẹ́ parẹ́ tán ta ní jẹ́ mọ̀ wípé ìlà ìjọba ń bẹ níbẹ̀ ọmọ onílẹ̀ ganan kò le è rí i bí ó ti ṣe parẹ́ tó | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹiyẹ igúnugún kìí ṣe ẹiyẹ lásán sí àwọn yorùbá ẹiyẹ tí wọ́n fi ń pa ọfọ̀ ògèdè àyájọ́ ni ẹiyẹ tí ó sì ní ṣe pẹ̀lú ẹbọ rírú ni wọ́n gbàgbọ́ wípé igúnugún ń jẹ ẹbọ kìí ṣe ẹiyẹ tí èèyàn gbọ́dọ̀ pa àwòrán encyclopedia britannica | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọdún shakespeare nlọ lọ́wọ́ ni àwọn eré orí ìtàgé mẹ́tàdínlógójì ní èdè mẹ́tàdínlógójì ni wọ́n gbé wá | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kò pẹ́ mọ́ bí ẹkún bá pẹ́ dalẹ́ ayọ̀ ń bọ̀ wá lóòwúrọ̀ máà sọ ìrètí nù akitiyan layé | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user • Ooo ma dupe pe won so ro é leyin, eni †i aiye ba †i pa †i bi aso to gbo nkan imi †i wo ni yen ooo! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
apeè ní ajínigbé nínú àhámọ́ fun odidi àádọ́ta ìséjú, wọ́n fi tipátipá jẹ́ kalọ sí ìrìn àjò asegbyinti, àìfọwọsí | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ní 1849, Ayaba Victoria fi Bíbélì tí a dì pọ̀ fi rán Henry Townsend láti fi jíṣẹ́ fún Aláké Ẹ̀gbá, ọba Gbádébọ̀. #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
and february osu erele | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
yoruba is first class language ko si elegbe e | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Yoòbá ní kí ọ̀tún wẹ òsì, kí òsí wẹ ọ̀tún lọwọ́ fi nmọ́. Ẹ̀mi náa ti tẹ̀lé e yín. Ẹ ṣeun modúpẹ́ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ta ló rí gẹ̀lẹ̀dẹ́ àti nǹkan mìíìn tó jẹ́ ti | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ni òwúrọ̀ kùtùkùtù ọjọ́ kan, ó tọ́ ìyá-a rẹ̀ lọ láti ṣ'àlàyé ọ̀ràn náà tí ojú-u rẹ̀ ń rí nílé ọkọ. Ó sọ fún ìyá-a rẹ̀, wípé ọ̀rọ̀ ọkọ òun ti sú òun, wípé òun kò leè farada ìhùwàsíi rẹ̀ mọ́. #MajeleToNPaOkunrin #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Aago yii ti baje saa, ara e lo dojuti lai se emi. Mo gbodo ra omiran ni kiamosa | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òjò ìbùkún là ń tọrọ... Èdùmàrè rọ̀jò ìbùkún lé wa lórí. Ọba òkè rọ̀jò ìbùkún lé wa lórí. Fún wa lówó àt'àlááfíà ara, k'á lè rójú ṣìkẹ́ ọmọ tá a bí o è! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Sábàbí aáwọ̀ àárín-in Ifẹ̀ àti Modákẹ́kẹ́. Aago 1 #IjaIfeOyo | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: #Yoruba Ilẹ̀ ati Odù - obinrin ni wọn. @user @user https://t.co/0KEnRMtoo9 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: E yon gbau! """"""""@user: Ogbeni,bawo lose ri ere boolu afese gba to waye larin orilede wa ati iko agba boolu Ethiopia...#2014WC… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Àgbà òṣèlú Ògbẹ́ni McCain ti fi ojú Ààrẹ Trump gbolẹ̀ ní ìlú Amẹ́ríkà. Wàhálà dé! Ààrẹ ti gbé fone rè kaná. #TweetYoruba htt… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#iroyin, #yoruba, L'Osogbo, Omisore atawon oree re ji okada, ni won ba foju bale ejo… https://t.co/0RlZI9voeb | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.