text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
Awon ajagun ta! @user ti sa'se, sa'se lai foju kan'run...... https://t.co/FeEwcVh9bu
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
1.Ọ̀rọ̀ wo ni a lè fi rọ́pò àrọ̀sìn? #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ǹjẹ́ o mọ́ wípé, ilẹ̀ Tápà ni Ìgunnu ti ṣẹ̀ wá? Egúngún kan báyìí tó ga ju ẹsẹ̀ mẹ́wàá, tó rí bọrọgidi wálẹ̀. #DidYouKnow #NjeOMo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
4. Kíni à ń pe àbùdá inú àwòrán yìí? #ibeere#Yoruba https://t.co/eedwBWX3PW
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Lẹ́hìn òkùnkùn biribiri, ìmọ́lẹ̀ á tàn. / After a pitch-dark night, most assuredly comes the dawn. [Darkness can't be…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn oń'fá náà ò gbẹ́yìn nínúu akitiyan àti dá àwọn ọmọbìrin wa padà. @user | #THISDAY: http://t.co/QO4qE5mwD0 #Bringbackourgirls
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ǹjẹ́ adúláwọ́ lé ṣe ẹ̀sìn kannáà tí fufun ń ṣe? Kò yé mi tó ni o, mo nílòo àlàyé. #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹni tó ńbẹ̀rù àti ṣubú, àti dìde á nira fún un. / Whoever is scared of falling will find rising pretty tough. [Nothing ventured, nothing gained; be bullish; take calculated risks.] #Yoruba #proverb
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
LONI OJO AJE, KI AJE WA FI ILE WA SEEBUGBE🙏🙏🙏🙏💯💖 👍👍👍👍💓 #aje #monday #loveoneanother❤️ #mercy #blessful #yoruba #culture https://t.co/sy65JcN8pc
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ole tori amala ba won gbe oku royo, o tori ejo elejo bawon dele oba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹ máa wòwá níran o jàre. A ò lè fara wé yín ní Poland lọ́hùn-ún. Òtútù tiyín mú yàtọ̀ :)
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bàbá kérésì ń gún yán ta ní fẹ́ jẹ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wọ́n ní ó fẹ́ẹ̀ẹ́ tó ènìà 300 tó ti ṣekú pa. Àìmọye ẹgbẹ̀rún ni wọ́n ti pàdánù ilé wọn. #Bopha #Philippines
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: E ba mi dupe lowo Olorun fun omo mi Ibukunoluwa ti o pe omo odun mewa l'oni @user @user @user http://t.…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
èé ṣe tí ó fi jẹ́ wípé ẹni méjì rèjì nìkan ló tari ìtàn sí ibùdóìtakùn ìdíje ìtàn kúkúrú èdè ilẹ̀ adúláwọ̀ ẹ dákun ẹ fìtàn ránṣẹ́ kí ẹ fẹ̀bùn owó ṣara rindin tàbí kí ẹ bá ni pín in kí ẹni tí ó bá nífẹ̀ẹ́ sí i ó ba gánánní rẹ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àṣẹ̀hìnwá ni a dín àwòrán báwọ̀nyẹn kù, tí a sọ ọ́ di ìsààmì tó dúró fún gbólóhùn. #EdeAbinibi #Yoruba #IMLD17
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọjọ ija kọ la n wa òogun aluwo #TweetYoruba #TweetYorubaDay
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Fún ẹni tí kò bá mọ̀, ewì alohùn tí a tún ń pè ní ẹ̀ṣà ni ọ̀rọ̀ ẹnu egúngún tí a máa fi ń yí ohùn padà, láti mú ohùn dún bíi ti ẹbọra; ohùn ará ọ̀run. #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ni ṣe lẹnú mi da ṣàká, ń kò pàko lana, burọṣì oyinbo lasán ni mò lo. Ẹ kàààrọ o. #ekaaaro #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ó yẹ ká sọ wípé ìgbésẹ̀ mẹ́rin ni britain ti gbé láti gba bini tí ò bọ́ sí i kí ti tó ṣe
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ní ọjọ́ oṣù ṣẹrẹ nígbà tí àwọn àjọ ìjọba tanzania bunge péjọ ní dodoma fún ìjókòó ìpàdé tí ó ṣáájú nínú ọdúnun ẹyẹ òwìwí kan fò wọ inú ilé ìpàdé ó sì bà sí orí ajá níbi tí ó ti ń wo àpéjọ láti òkè téńté
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
nkan ti e hun so fun wa nipe kii awa omo yoruba fipa ta ip
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
gba fun baba nile ni gba fun gbada loko ara oko ti o ba fee je buredi yoo fi isu ranse sile
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àánú àwọn tó ṣe mí ní #Gaza ni àwọn tí ò mọwọ́-mẹsẹ̀. Ọlọ́run Ọba gba àkóso. #Israel #Hamas
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
tí wọ́n bá bọ òrìṣà tàbí orí tán obì ni ó ma jẹ́ ohun ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ láàárín ẹni tí ó ń bọ òrìṣà tàbí orí pẹ̀lú òrìṣàorí náà èyí tí wọ́n ma fi mọ̀ bí ohun tí wọ́n ṣe jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà wọ́n ma fọ́ obì náà sí awẹ́ tí wọ́n ma wá
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo wo eré Lionheart ní ọjọ́ kẹẹrìn-in lé ní ogún,oṣù kejìlá, mo tún padà lọ wò ó ní ọjọ́ kòkan lé ní ọgbọ̀n oṣù kejìlá, Bẹ́ẹ̀ni,o dáára tó bèe! Gbogbo ènìyàn pàtéwọ́ fún eré náà.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
fíìmù yìí jẹ́ aláìdùn púpọ̀. Ìrẹ̀wẹ̀sì púpọ̀. Púpọ̀ púpọ̀.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Nje e ti gbo o ri? wipe EEWO ni, ni ile Yoruba 'ki obinrin o maa fa aso lale'?.......E je ki n koko ki yin niki... htt…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀gbẹni Amos Ọlátunjí Pópóọlá jẹ́ ọkan nínú àwọn márùn-ún to yege jùlọ nínú ìdíje ẹ̀bùn ìwé kíkọ Ẹgbẹ́ Àtẹ́lẹwọ́ fún iṣẹ́ wọn tí àkọ́le rẹ̀ ń jẹ́ """"""""""""""""Akínkanjú Ọdẹ Nínú Igbó Àmọ̀tẹ́kùn"""""""""""""""". #AtelewoPrize #Atelewo #Yoruba #YorubaBooks https://t.co/6wxOHMxT62
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
awa na la fa olorun yio gba fun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ojúmọ́ rere mọ́ wa lónìí *16* oṣù 11. Ire Ajé oníso ibòoji mẹ́rìndínlógún á wá wa wálé lọ́láa Elédùà. Ẹ pé á á ṣẹ!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àròká = aláròkà ìsọkúsọ = onísọkúsọ ìnákúnàá = onínàkúnàá yọ ọ̀rọ̀ mìíràn láti inú ọ̀rọ̀ wọ̀nyí ahesọ ẹlẹ́yà
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ọlọ́run má jáa rí irú èyí mọ́ láí-láí!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Màgódò ❌ Máàgódó ✔️ Máà-gún-odó ni a sọ di MÁÀGÓDÓ. Máàgódó l'ó tọ̀nà ní pípè. Máà gún odó l'ó di MÁÀGÓDÓ, àṣìpè ni MÀGÓDÒ. #Oruko #Yoruba #Magodo #Lagos
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
original cooking kooking pot kokoshunimo ikoko dudu always cooking nor cooking ire o yoruba ire owo ire omo ire aikubaale oro se ire fun gbogbo wa loni amin
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user ewé efirin ni, orìíṣirìíṣi ló wà. Wẹ́wẹ́ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
inú mi ì bá dùn bí ẹní láyin bóbáṣepé èdè yorùbá ni ẹ fi kọ kíni yìí
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
📷Aare Ona Kankanfo ati gomina @user https://t.co/yqqiPJfHhJ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eku dede asiko yi ajinde ara yio ma je
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user Kí olúkálukú yáa ṣe jẹ́jẹ́ o. Ó d'ọwọ́ Ọlọ́run.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Abala ke̟rin. A kò gbo̟dò̟ mú e̟niké̟ni ní e̟rú tàbí kí a mú un sìn; e̟rú níní àti ò wò e̟rú ni a gbo̟dò̟ fi òfin dè ní gbogbo ò̟nà.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ojúmọ́ ire... A kú ìsinmi òní🤗🤗🤗 Ẹ rántí láti tẹra mọ́ ohunkóhun tí ẹ bá mọ̀ ọ́n ṣe dáadáa. Ẹ má ṣe kánjú ju Ẹlẹ́dàá lọ…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òròmọdìẹ ni ọmọ ẹdìẹ, kí ni à ń pe ọmọ kìnnìhún? #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
sèsé ò wọ̀pọ́ lóde ònìí eku oko a máa fẹ́ràn an rẹ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user ede Yoruba wa ninu #PETSS.. kii se ede Geesi nikan ni a fisibe
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìwúrí ló jẹ́ fún mi ní òwúrọ̀ yìí o ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìwé ìròhìn ni wọ́n gbé àwòrán awọn ọmọ wa yọ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ma ná wọn lówó díẹ̀ láti gbé kalẹ̀, pẹ̀lú àwọn irin iṣẹ́ inú rẹ̀. Àwọn Oníṣòwò ńlá yìí, má sọ bí wọ́n ṣe fẹ́ kí àwọn alágbàṣe wọn ṣe àwọn iṣẹ́ wọn, ní gígùn, àwọ̀ àti bí ó ṣe ma rí lọ́wọ́. Orúkọ tí wọ́n ń pè àwọn alágbàṣe aṣọ ni """"""""Alágbàwun""""""""
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
A tún dé lónìí Ọlọ́run Ọba. #Olorun #Olodumare
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orí eékún ló di orúnkún ìyẹn ni àwọn eléèbó ń pè ní knee cap eékún ni knee
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Eégún ò dé 'Jẹ̀bú rí. Iba Aíbadé. Iba l'ó k'éégún wọ'gbóo Rẹ́mọ. #Oriki #Itan #Yoruba #IYIL2019
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ̀ka Ìmọ̀ Ìjìnlẹ̀ Ìṣẹ̀dá Ẹ̀dá Alààyè ilé ìwé ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ àti ìmọ̀ ẹ̀rọ Covenant ní ìpínlẹ̀ Ògùn ṣe Ìwádìí nípa àgbálùmọ́. #Agbalumodun🍊
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn obìin mìíìn ẹ̀wẹ̀wẹ̀ ò ti ẹ̀ ní ọmú àmútọ̀runwá mọ́, ọmú oníke ni wọ́n ń gbé kiri. Irúu wọn ò ní le è fọ́mọ lọ́yàn. Òṣì ò da ńlé pákó.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
nkan ti bàjẹ́ pátá pátá pátá ní #Nigeria!. Àbí báwo ni wọ́n ṣe tún jẹ́ kí #DanaAir padà?
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ǹjẹ́ o ti ṣetán láti tẹ̀lé àwọn ìlànà tí mo ti là kalẹ̀ wọ̀nyìí ìyá bí ọmọọ rẹ̀ léèrè bẹ́ẹ̀ ni ìyáà mi ó dá ìyáa rẹ̀ lóhùn
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: A kí gbogbo ẹ̀yin olólùfẹ́ Àbáláyé Nigeria kú àyájọ́ ọdún olólùfẹ́. Àṣèyí ṣàmọ́dún o. We gret all our lovers, Happy Val…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Bí aṣọ́ bá ṣá, á fàya, bí ilẹ̀ bá ṣá, Ilẹ̀ á di àkọ̀tì, ọjọ́ tí ìfẹ́ bá ṣá ni tọkọtaya yóò yàgò fún ara wọn. #EsinOro #Yoru…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Àìlèsọ̀rọ̀, ìbẹ̀rẹ̀ orí burúkú ni"""""""""""""""". Translation: """"""""""""""""One's inability to talk is the beginning of his misfortunes"""""""""""""""". Lesson:…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìjọba #Nigeria l'áwọn mọ'bi tí wọ́n wà, àsìkò ò sì tíì tó kí wọ́n ó lọ gbà wọ́n nígbẹ̀sìn #BringBackOurGirls :(
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ekabo sori eto oju orun to eye fo lai fara gbara won
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Olufunmilayo - """"""""God gave me joy"""""""" #enamelpin #pindesign #pingame #Yoruba #olufunmilayo… https://t.co/uLvSUOik3w
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
o ṣe é
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Awon amuni buni eran ibiye #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ah! @user Ẹ mà ṣeun o. Àṣìkọ ni. Ẹ̀yin ọmọ ìpínlẹ̀ Ògùn ẹ kú àìbínú :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọ wa ni ó yẹ kí o je iwuri fún wa, gbogbo ènìyàn ló mọọ gẹ́gẹ́ bíi olotito ẹ̀dá tí kò sì ní abawon kankan nínú ìwà ajebanu. Ẹ jọ̀wọ́ ẹ fi ọgbọ́n inú dibo yìí. Àsìkò rèé láti kọ fifi imotara ẹni nìkan se ọ̀rọ̀ @user
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òwe yìí ń sọ fún wa pé ijó ni ti Agẹmọ, àmọ́ gbogbo Agẹmọ kọ́ ni oníjó. #Irinajo #Ijebu
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""@user: Kíni """"""""Ọ̀jáàgbá""""""""? #Ibeere"""""""" Ada kekere ti a fi san oko paapaa ju lo awon omo ile-iwe @user @user…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
omo dara ti egan koh toni fe shemi le she
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
láti ọwọ́ ẹgbẹ́ aláwàdà tí moses ọláìyá ẹni tí a mọ̀ sí bàba sàlá wà lára wọn sórí afẹ́fẹ́ ní kóòtù aṣípa láti ọwọ́ dúró ládiípọ̀ náà bọ́ sórí afẹ́fẹ́ ní ọdún lẹ́hìn tí ìjọba ológun gba agbára wọ́n yí orúkọ wntv padà sí
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọ ẹran ń pọ̀ sí i lójoojúmọ́. #AwokoseIranu
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eni tio ba tiju fun wa lao tiju fun awao o tiju fun enikan kan mo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
òkè lẹmu ńru sí òkè la ó ru sí lọ́lá òní tí í ṣe ọjọ́rírú a ò ní kú a ò ní rùn à á rójú ráàyè ṣehun re
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Èrò ti pọ̀jù níbí náà. Ṣùgbọ́n ọgbà tí ọjà náà wà tóbi dáadáa. Mo gbádùn ẹ̀ gan-an ni.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user ose yi a tura ko ni le Koko Mo mi #yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí Ìpọ̀nrí ti ń dàgbà, kò yí Ìdánimọ̀ rẹ̀ padà. Ìpọ̀nrí so pọ̀ mọ́ iyè àti èmi èèyàn. Bí ọmọ tí ń dàgbà nínú ìyá rẹ̀, Àjàlá ni ó ń mọ́ Orí/Ẹlẹ́dàá ọmọ náà, kí wọ́n tó bi. Ọ̀rúnmìlà wà nílé Àjàlá ní ìgbà tí ọmọ ń yan Ẹlẹ́dàá, kí wọ́n tó bí.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Níjeèló, kókó-inú-ìwé ìròhìn ní obìnrin kan f'ìdí ọmọ rẹ̀ jó ẹ̀rọ ìdáná torí ó tọ̀ọ́lé. Orí bíbẹ́ wá ń ṣ'ògùn orí fífọ́? #O…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: 4. Bí Ọlọ́run bá fẹ́ẹ́ bá wọn sọ̀rọ̀, Ọlọ́run lè kàn fi èrò náà sí ọkàn wọn, @user @user @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orisirisi ni a sa n gbo ni orileede naijiria yii awon agbebon tun pa osise eto ilera mewa ni ilu kano
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Afẹ́ ni Afẹ́, Abíọ́dún ni Abíọ́dún. Wálé ò kí ń ṣe Whaley, ó tì o. Títí kọ́ ni Teetee. #KoOrukoDaadaa
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọ̀nà kan tí a lè gbà mú afẹ́fẹ́ àyíká wa dára fún ìlera tó péye ni igi gbíngbín a ò gbọdọ̀ gégi ní ìgékúgèé
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: #tweetinyoruba,@user @user @user Ni iranti baba wa Adebayo Faleti fu ise ti wan se fu èdè wa ht…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user Akanni àbí akàn ni? Ìyàtọ̀ ń bẹ.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: E ku ise ribiribi @user. Odun pupo lati ma a ri tweets ni ede your bank!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Iṣé ńlá lọ sínú rírò rẹ ẹ̀, ó tún wá kún fún iṣé takuntakun. Eyimofe fún wa ní ìrírí tó dáju nípa bí ìgbésí ayé àwọn ará Èkó ti rí
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ki enikeni mase daaba ati koja lori ona eko si ibadan sunkere fakere to wa lona yen o se ko loni
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
amin o odun yi a yabo fun wa o aori batise aori ona gbe gba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òjò nrọ̀. Ṣeré nínú ilé. Má wọnú òjò. Kí aṣọ rẹ. Má baà tutù. Kí òtútù má baà mú ẹ o! #yoruba #orin #ojo #otutu
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Akótilétà ìjọba Nàìjíríà! Ṣé ẹ nwo àrà tí wọ́n ndá ní #Ghana? Ẹ yé kó dúkìá ilẹ̀ wa tọọrọ fún gbogbo aráyé mọ́ o!
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ojo ife ro lemi o ara mi wa lona o.. #orinaladun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìtàn odò Yewá fẹ́ bá ti Yemọja mu; wọ́n lulẹ̀, wọ́n di omi. #Gelede #Yoruba #Ifa
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ kú ajálẹ́ ńbí o bóo níṣẹ́ òní mo lérò wípé ajé sọgbá jẹ a ò ní ṣe é tì o àṣeyè tálákàn ń ṣepo la ó ṣe lọ́láa wáídù lókè
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bákan náà ni àkọsílẹ̀ ṣàlàyé wípé ọmọ Houegbadja tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Akaba lọ bẹ olóyè kan ní Gédévi tí oókọ rẹ̀ ń jẹ́ Dan wò, ó sì béèrè ilẹ̀ lọ́wọ́ọ rẹ̀ láti fi kọ́ ààfin, eléyun-ùn fún Akaba nílẹ̀ tí ó béèrè fún láti k'áàfin. #OgunDahomeyAtiEgba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ìyá àbúrò! Àkàrà rèé! Ye!
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀bún ríkú ọkọ dìrọ̀ mọ́n. #EsinOro #Yoruba @user #June12
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#TweetYoruba 2014 - Saturday 1st March 2014 Yoruba to so wipe ile la n wo kia to s'omo l'oruko o kuku puro http://t.co/VV3pEE5sUx
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọ Yo'bá fẹ́ simin agbaja. Ó dàárọ̀ ọ̀la. #yobamoodua
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user: @user ogbeni yobamoodua e ti tumo oruko mi fini fini. E ti gbaa ju.""""Mo-rí-ohun-kẹ́ :)
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
O tún yá o! èyin Omo káàrò òjire o, àlọ́ tòní re o, kíni ìdáhún ti yín o. #talk #folklore #folktales #theyorubapeople🇳🇬 #yoruba #aloo #blackpeoplememes #cultur #àsàyorùbá #àsà #traditionalart #òwe… https://t.co/C4Klk8TNmZ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn àlejò ti bẹ̀rẹ̀ sí í dé sílé wa. Àmọ́ kò sí iná. Ọlọ́run ṣeun ṣá, atẹ́gùn nfẹ́. Ìta gbangba làá fi ìkàlẹ̀ sí.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí #IEDC bá pa iná. Há à!!! Lẹ óò gbọ́. #Nigeria
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìrọ̀rùn ló bá dé ó kù sí ọlọ́pọlọ ọmọ lọ́wọ́ à ti yá a lò kó múu lò kí ó múu sà bí oògùn
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train