text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
RT @user: Amin!RT @user: Iṣu ọmọ á jiná fún wa jẹ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Òótọ́ korò, ṣùgbọ́n bí a bá gbé itọ́ ọ rẹ̀ mì, a máa ṣe ara lóore. / Truth is bitter, but if it can be swallowed, it i… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Aládàáni is private (ilé-ìwé aládàáni - private school, ilé iṣẹ́ aládàáni - private company) #InYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
2. Ọmọdé kan wá pọn'mi lódò, àmọ́ odò ti gbẹ, ẹ̀hìn tí ó wò, Hinderer l'ó rí tí ó ń lọ. #Yoruba #Ibadan | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó yọrí sí àìlọ́pọlọ àti àìkún ojú òṣùwọ̀n. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ìkùnà tí ó wà nínú ẹ̀dá náà panilẹ́ẹ̀rín. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Eré yìí jẹ́ eré òṣèlú tó dára jùlọ ní ilé adúláwọ̀. . Ẹ jẹ́ kín bẹrẹ́ láti ṣe òṣùbà fún àwọn òṣèré tuntun ti won fi owo si aseyori Eré oselu yi | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: """"""""@user: Jíjí tí mo jí, mo fọpẹ́ f'Ólú Ọ̀run. #ekaaro"""""""" Ekaaro o Alakowe, ojumo re lo maa je fun wa o, amin. Hop ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
irun ṣùkú yìí táa tún ma ń pè ní alágogo ni ọbintun tí ń relé ọkọ máa ńdì àrà ni oníṣùkú lè fi irun un rẹ̀ ṣe | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Lóòótọ́ òwú ni a fi ṣe kíjìpá àmọ́, a máa nípọn bí awọ @user @user #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọpẹ́ ni f'Ólúwa Ọba Apọnmọnmáwẹ̀hìn. Pọ̀n wá Olúwa f'ọ̀já múwa káa má baà ré lulẹ̀ lẹ́hìn rẹ o. #ekaaro | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Njẹ o mọ? Njẹ o mọpe kò lẹtọ fún ọlọpa ọkunrin lati wa ẹru tabi ara obinrin? O lẹtọ ki ọlọpa ọkunrin yẹ ọkunrin wo, ki ọlọpa obirin si yẹ obirin wo, lai si iwa palapala kankan. #Yoruba #EndPoliceBrutalityinNigera #EndSARS #EndSWATNow https://t.co/Gw21o3sBzY | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user iṣẹ́ ńlọ lórí ẹ̀, àti pé igi Kan ò lè dágbó ṣe. Blog wà, yẹ pátákó àlàyé nípa mi wò. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eyin loro, toba tijabo! Kose ko mo #Yoruba adage https://t.co/tlCBCwjCm0 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kílagberò àtọlọ́pàá fi jọra owó oríta agberò tún ń bá ọlọ́pàá gbowó oríta ọmọìta ti fa èkó ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ ó ṣe | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìsimi àpàpàndodo là ńgbà, kàkà kí a parí lọ́dún nìí, ó tún di ọdún tó'mbọ̀. Háà! Ó mà ṣe o ☹ #ASUU #IfNotForAsuu #Nigeria | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Asinla ni ti Agbonri. Akanamagbo ki npa odun je.""""""""@user: Mo dúpẹ́ fún àlàjá oṣù Ọlọ́run, oṣù tí nbọ̀ yìí dọwọ́ r ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Orí gbé ire gbogbo orígun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin àgbá ayé tọ̀ mí wá. Ire Ajé, ire ọmọ àtire àlàáfíà. #Iwure | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kò fọwọ́sí. Dejavu jẹ àpẹẹrẹ eré Yorùbá | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: Jọwọ dariji mi, Yoruba mi ko dara. Nwa fun awọn onijo lati jo Crypto Crawl fun aye lati win 200 #XRP. Fi fidio ranṣẹ… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Alatunse lomo atunse ara re"""" #Yoruba #OdodoOro | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
O dára tí ó bá gbádùn kókó- òrò eré àgbéléwò náà. . Tí ó bá jẹ́ pé ķókó òrò náà ló gbádùn dájúdájú eré àgbéléwò tí ó dára ni.. . Àmọ́ bí fíìmù náà ti ń lọ ti fàà jù. Níṣe ló dà bíi eni wípé wọ́n fẹ́ tẹlè múyé. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Nìkan ní ìpò àwàdà Nollywood gbòòrò. Ṣé ó ní ìdánilójú nítòótọ́. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
A fi ọ́ jọba ò ńṣàwúre o fẹ́ jẹ Ọlọ́run ni? | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
nigbana mole funyin laridaju nipe bope boya gbogbo ero okan wa gbogbo ero n gba wa a wasi imuse sugbon a ma ni lati şe opolopo suuru nitori gbogbo lamo pe won o ko rome lojokan ️ moshood | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
òkèòkun kì í dùn kátukọ̀ máà lórí padà bọ̀ ṣoríire lọ́hùn ún kí o kóríire ọ̀hún ran naija àwé ò dákun mọ́ gbàgbé ilé | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eni ti ko ba gbo ti enu ega oun ni yoo so wipe o n paato #Yoruba #proverbs | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bí ẹlẹ́tàn bá máa wí, á ní “kíkọ ìṣẹ̀lẹ̀ sílẹ̀ kì í ṣe àṣà àwọn baba wa”, wọ́n á bu ẹnu àtẹ́ lu àwọn alálẹ̀. #EdeAbinibi #IMLD17 #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Oun kàn tí ó lè wù yàn jù nínú eré obìnrin tí à ń pè ní èémí ni àwọn àwọ̀ tó yanrantí, wọ́n fún eré náà ní ìtẹ̀jáde tí ó gbáyì. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ìbà f'Ólódùmarè ọba Aṣèyíówùú. Ọba Apani, Ọba Ajíni. Mo ríbá mo ríbà k'íbà mi ó ṣẹ. Ẹmọ́ mi jí ire lópòó ilé, mo ṣoríire, Ẹlẹ́dàá mo dúpẹ́! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Nínú ọwọ́ ọ̀tún àti t'òsì, èwo la máa ń lò jù lọ? Ẹ̀kànànkan lọwọ́ òsì ń ṣiṣẹ́ (àyà fi ọlọ́wọ́ òsì) làwọn aláṣetì fi pè é ní ọwọ́ àlàáfíà. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
afárá àbí afá ni à ń gbé sórí odò kòtò afònífojì láti tẹ̀ mọ́lẹ̀ kọjá sódi kejì nílẹ̀ẹ yoòbá nígbàanì | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀rọ̀ tí kò l'agbára, àfihàn ìjà tí kò múná d'óko | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
olódùmarè agòtún tó dá ewéko àti ẹranko gbogbo mọ ìdí tí ó fi dá wọn bẹ́ẹ̀ èwo ni ti àfikún àyọkúrò àti àdàmọ̀dì àwọn oúnjẹ wọ̀nyí nítorí owó àwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ń fa àìsàn tí kì í sàn bọ̀rọ̀ sí wa lágọ̀ọ́ ara | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èyí l'àwọn bàbáa wa rí tí wọ́n fi ṣ'àpèjúwe pé """"""""wọ́n ń kí ọ̀run/Ọlọ́run"""""""", àwọn t'ó ń kí-ìrun; kírun. #Yoruba #Irun | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
YORUBA CURENTLY UNDER FRINGE ATTACKS BY FULANI MILITIA. #KeepitOn #yoruba #YorubaNationNow #EndNigeriaNowToSaveLives Eyin agbalagba iranu playing greedy politics with the future if yorubaland E ni ku sibi ti aso yin wa. cc @user @user @user https://t.co/4JQHzEhfIe | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ̀wẹ̀ so ládúgbò yìí o! #Ijebu #Ogun http://t.co/w9EgGZq1B0 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
huum o ya so itumo gbolohun yi i to ba je omo yoruba ponbele ni e oku onika kan abi okun onika mewa ewo n | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
yankolu yankolu ko wa tan bi gbe ogbeni aye dee sanle ni se ni aye dee yoke ogbontarigi olofofo linda ti pada sori afefe o | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
a lá a gba òmìnira síbẹ̀ owó ilẹ̀ òkèèrè dollar ni a fi ń ṣe òwò a sì ní owóo ti wa bí àgbo jẹ̀dí bá hán dollar ni | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kosi ohun ti a mu waye ko si ohun ti a ma mu lo si orun ile aye ofutu fete nitori na e je karanti iku tápá ò le dìde | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
bí a gúnyán nínú ewé bí a sebẹ̀ ńnú èpo ẹ̀pà ẹni tó máa yó a yó àgbo dára mu ún | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user ó tì, àwọn nǹkan wọ̀nyí ni a fi jẹ́ ìran Yorùbá. Digbí ni ìṣe yìí wà láyé ìjọ́hun, ẹ̀yìn tí òyìnbó dé ló parun. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ní àárín ọgbọ̀n ọdún ti o délé ayé, o ti ṣe gudugudu méje àti yà yà mẹ́fà ní ìmáyé rọrùn ọmọnìyàn níbi gbogbo ní abúlé àgbáyé. Ó ti so ayé pọ̀, okòwò ti rọrùn fún àwọn olókòwò. Èrò tí ó wà lórí ayélujára pọ̀ yamùrá. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fún gbogbo àwọn ÌYÁ káàkiri àgbáyé. Ẹsẹ́ púpọ̀ fún isẹ takuntakun yín lórí wa. @user omoyoruba7in3 #yorubademons #yoruba #ÈdèYorùbáRewà https://t.co/M2y9mqMwiK | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user ẹ pàtẹ́wọ́ fún'ra yín. :) | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bí nkan ṣe rí yìí, njẹ́ ó pọn dandan kí a kópa nínu hílà-hílo ẹ̀bùn rírà ọdún #Kérésìmesì ? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọmọ ò ní gọ̀ gọ̀ gọ̀ kí ó máà mọ orúkọ rẹ̀. Èdè ẹni ni ìdánimọ̀ ẹni. Ọmọ Yoòbá ni mí, mo sì mọ rírìi èdè abínibí. #EdeAbinibi #Yoruba #MotherLanguageDay | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àmọ́, arapa ogun Fúlàní tí ó mú wa pàdánù Ìlọrin látorí ìwà àìnítẹ̀ẹ́lọ́rùn Àfọ̀njá. #AareOnaKakanfo #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ki ní yìí tiwa ni yàtọ̀ sí kiní yìí tèmi ni bẹ́ẹ̀ bù fún mi kí n bù fún ọ lọ̀pọ̀lọ́ ń ké lódò ohùn àgbáyé ń fẹ́ ìrànwọ́ láti tẹ̀síwájú nínú iṣẹ́ ìlú tí ó ń ṣe láìsí owó kò sítẹ̀síwájú ìwọ náà lọ́wọ́ sí i | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wọ́n níkú akọni ní í pa akọni; ikú omi ní í pa ọ̀mọ̀wẹ̀; òwò t'ẹ́dàá bá mọ̀ ní ṣẹ́ ẹ̀dá lẹ́yìn. #AdebayoFaletiODigba #Yoruba #OmoYoobaAtata | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òní (05-07-2019) ni ọjọ́ tí àwọn Alágẹmọ ń lọ sí Imọsàn. Èyí tí ó túnmọ̀ sí wípé, òní ni ọdún Agẹmọ bẹ̀rẹ̀. A ma gbé àwọn òwe, orin àti ọ̀rọ̀ tí ó dá lórí Agẹmọ yẹ̀wò láàárín ọjọ́ méje ọdún náà. https://t.co/caJ2734Xmc | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìròyìn Langbasa lórí ìkànnì @user Àwọn Àkọlé lásán. #Yoruba #Asa #Yoruba #Rédíò #Yoruba_Broadcaster #Iroyin_Langbasa #Awon_akole #Igbohunsafefe #Agbohunsafefe bbcnewsyoruba https://t.co/pa96TMK5mE | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
a tú dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn alátakò wá náà, a ó gbọn tán bẹẹni a ó mọ tán, a ń gbìyànjú ni, a ó sì ní rẹ̀wẹ̀sì láti tún moose si, laipe yii a ó gbé àmì idanimo wá jáde fún gbogbo yín. https://t.co/LEqsIFKqsR | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
😪 Ṣé o rẹ mi? Bẹẹni! Ṣugbọn mo o lè lọ sùn, nítorí pé mo fé ṣé nkán lọpọlọpọ. #PolyglotTweet #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìdí èyí ni a fi máa ń ní, ẹyin lóhùn, bí ó bá bọ́ sílẹ̀, kò ní ṣe é kó. Ipasẹ̀ èdè sì ni ọ̀rọ̀ fi ń bọ́ lẹ́nu. #EdeAbinibi #Yoruba #IMLD | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé nítorí ìṣe bí omi àtisánmà wá ṣe máa ń ro bíi omi inú agbọ̀n/ihò ni Yorùbá fi pe omi nì ní """"""""òjò"""""""" - ohun ń jò? #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kùtùkùtù kìí jóni lẹ́ṣẹ̀ bí ọ̀sán òwúrọ̀ la wà yí kí olúkálukú yáa tètè múra síṣẹ́ o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àgbà tó diyọ̀ eèpẹ̀ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Erin ibi kan èlírí ni ní ibòmíràn. / An elephant (what is significant) in one place is a tiny mouse (insignificant) in… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
.@user oku ori ire. Oti lo GBA lowo e ko mo lo fun @user A paro wa fun @user ki won ye se slow Eti won di si ikilo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ko sí ipele kan nínu eré orí ìtàgé tíì àwọn olùwo eré yìí kò b'áwọn lọ. Fún ẹni ti kò bá mọ ju èdè gẹ̀ẹ́sì lọ, e wo eré yìí, eré orí ìtàgé tí ẹ máa wò lẹ́ẹ̀kansi ni. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
náà jẹ́ ọkàn lára ayánilówó fún òwò ẹrú | | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ejo se oluko yooba ni yin ni | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹni a nbọ́ kòlè mọ̀ pé ìyàn mú. https://t.co/pMARvzWBEx | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọmọ ọlọ́dún yẹra wò #Yoruba #Oduntuntun2015 http://t.co/rnSoaJcYZp | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìdí iṣẹ́ ẹni la ti ń mọni lọ́lẹ, bẹ́ẹ̀ òwò tí ẹ̀dá bá mọ̀ ní í ṣẹ́dàá lẹ́yìn, òwò ẹran-ọ̀sìn tí wọ́n ṣe ní Gobir náà ni wọ́n bá dé ilẹ̀ Yorùbá (èyí tí í ṣe Ọ̀yọ́-ilé). #Darandaran #ItanFulani #Nigeria | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ẹ̀dá tó mọ ìṣe òkùnkùn kó má ṣe dá òṣùpà l'óró. (Whoever knows the ills of darkness should not harm the moon.) #yoruba… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wọ́n ṣe é fún èrè ìtàgé tí ó dun. Kò dára ní àwọn apá kan tí ó sì nira fún mi láti tesiwaju nínú wíwò rẹ̀ Ń ó lè gbà enikeni nímọ̀ràn láti wo ó | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àfojúsùn sí rògbòdìyàn tí ó bùáyà yìí ṣe àfikún ìròyìn ọ̀kan ò jọ̀kan àti ìlànà-àgbékalẹ̀-ìlú láti jẹ́ kí àwọn nkan hàn sí ọ̀gbẹ̀rì. sinemá àgbéléwò tí ó tẹ́ni lọ́rùn ní ipele tí ó pọ̀ ni, ó sì jẹ́àṣeyọrí pàtàkì fún ilẹ iṣẹ sinemá àgbéléwò nigeria tí ó ṣì wà ní ìkókó. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
IS IT YOUR RIGHT? SE ETO RE NI? (Yoruba Nation) https://t.co/NiROXfbSS0 via @user #oodua #yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọdún òkè ìbàdàn ó jẹ́ ọdún tí àwọn ará ìbàdàn ma ń ṣe ní ìrántí ìtẹ̀dó ìlú ìbàdàn àti ní ìrántí àwọn tí wọ́n tẹ ìbàdàn dó ọdún yìí ma ń wáyé ní oṣù ẹrẹ́nà ní ọdọọdún | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bó tilè je pe wón kà á sí eré tó ń ba ni lẹ́rù, 'Bridal Shower' kìí se eré bẹ́ẹ̀. Ereé rádaràda ni, kò ní ìtumò rárá. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Sahara ni wọ́n gbà wọlé gbà padà, eégún ẹrú t'ó kú s'ọ́nà ń bẹ l'ọ́nà nínú iyẹ̀pẹ̀ dònìí. #nigbatiwonde | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
to do is máa ká ṣáṣáà máa ṣe rere | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user E seun o. A ku imurasile odun, a de bawa layo o. @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó dùn móni. . Mo gbádun eré náà. Eré náà àti ìtàn náà Dára púpọ. Mó rí gẹ́gẹ́bí oun tí ó múmi ronú Lórí ọ̀rọ̀ ìgbèsí ayé– èyí dájúdájú yíò je ìlanilójú fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí wón ń to ṣe ìgbéyàwó. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
ó jẹ́ àṣà nílẹ̀ẹ yorùbá kí ìyàwó ó bọ̀wọ̀ fún àwọn ẹbí ọkọ pàápàá ọmọ ilé tí ó di èèwọ̀ fún un láti la orúkọ mọ́ wọn lórí orúkọ bíi dánkúlúbọ́ ìdí ìlẹ̀kẹ̀ fún wa lápẹẹrẹ irú orúkọ bẹ́ẹ̀ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kí adé túbọ̀ pẹ́ lórí o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
iṣẹ́ náà léè jẹ́ gígé igi tàbí, kí wọ́n wá kọ ebè lórí oko àti àwọn iṣẹ́ oríṣi. Ọ̀fẹ́ ni gbogbo iṣẹ́ tí wọ́n bá ṣe lórí oko náà ma bá dé. Iṣẹ́ ọ̀wẹ̀ kìí kọjá ọjọ́ kan tàbí méjì (ó pẹ́ jù). Àwọn àgbẹ̀ tí wọ́n ní ọkàn láti ṣe ohun ńlá tàbí àwọn tí àgbà | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
3. Kọ òǹkaye yìí lédèe Yorùbá pọ́ńbélé 67 = #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: 5. Jésù ni Jesus lédèe Yoòbá. Sámúẹ́lì ni Samuel. Jósẹ́fù ni Joseph.____ ni Satan lédèe Yoòbá. #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user @user @user Eyan mi pataki pataki, olubadamoran si Gomina mi, omuoluabi nbe lara re @user mo ji… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
2 nigba ti ara ilu ba ko lati fun won lowo riba ti won beere fun. @user @user @user #TweetinYoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àyájọ́ Ọjọ́ Èdè Abínibí. Ọmọ #Yoruba dà? #EdeAbinibi #MotherLanguageDay http://t.co/9WJPBZ9d5F | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
peter ji okada ileese dove lo ba foju bale ejo tolulope emmanuel peter | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
13. #PariOweYii: Obì aláwẹ́ mẹ́ta... #ibeere #Yoruba #Owe | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Ire loni Oba Edumare. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kaka ki nbi Egba obun Maa kuku bi okansoso Oga Maa fi yan araye loju Ma rohun fi gberaga #Yoruba Our philosophy on parenting needs to be reviewed as a people because at the base of our cultural beliefs about... https://t.co/bOGSlX7CeP | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ilà wo lò ń lò | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
À ń kí ara wa kú u ÒMÌNIRA, àmọ́... 📌Ṣé lóòótọ́ ni wípé a ò sí lóko ẹrú mọ́? 📌Ṣé lóòótọ́ ni wípé a gba òmìnira? 📌Ṣé lóòótọ́ ni wípé a ò sì lábẹ́ àwọn èèbó amúnisìn mọ́? 📌Ṣé lóòótọ́ ni wípé a ti dá dúró gedegbe? Ṣé lóòótọ́ ni? #AyajoOjoOminira #Naijiria 🇳🇬 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ọ̀gbẹ́ni Káyọ̀dé. Ẹ kú ọjọ́ ìbí o. Ẹ̀mí á ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ rẹ̀ láyé o. Ẹ ó dàgbà darúgbó o. Lágbára Ọlọ́run Ọba. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user ohun to wa seni laanu ni wipe awon ti a gbemi le lati sooto, ohun ti awon naa o je ko je ki won gbon #naija | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
hmmm òwe lẹṣin ọ̀rọ̀ ẹ ẹ́ rímíì pa o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: B'ọ́kọ̀ bá r'òkun, b'ó r'ọ̀sà, ó di dandan k'ó f'orí l'ébùúté. Èkó ilé yá! | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ṣé ó tán àbí kò tán ilẹ̀ òkèèrè ni ọ̀rẹ́ mi olùkọ́ orlandes ti ń fi èdè yorùbá tàkùrọ̀sọ pẹ̀lúù mi kò ha tán bí | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
... A Pee Kii O Waa Jee Oye ... Koo Moo Ohun Tii Oju Afobajee N Rii ... #Yoruba Dun Nii Ede ... Speak Your #Language ... #OKAY! | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
orí agbe ní í gbére padè olóko orí àlùkò ní í gbére padè ọlọ́sà orí mi tètè gbé ire padè mi lọ́nà ìpọ̀nrí máa gbọ́ o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kí ara ba fúyẹ́ láàárọ̀ bí a bá jí omi tí ó lọ́ wọ́ọ́rọ́ ni a óò mu èyí yó po inú ẹni pọ̀ imí ara yóò jáde lẹ́rọ̀ ẹ kú ojúmọ́ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ilé Odùduwà ti dilé ìjọsìn. Àwọn irúnmọlẹ̀ ti gba Jésù... Nǹkan ṣe! #IleIfe #Ife #Oduduwa https://t.co/LxDxo6dC5f | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.