text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
RT @user: Olorun toda awon oke igbani, Eyin nimo fi ope mifun. Tani n o tun gbega biko se baba loke, tani n o tun fi gbogbo ope mi fun? … | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ ká alẹ́ o a ò ní ráburú lọ́dún tuntun o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ẹ wo àwọn ike, ìgò àti páálí lábẹ́ ewékot http://t.co/3P47mNHf | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọmọ ọlọ́kọ̀ nílé ìṣeri iwájú ọlọ́kọ̀ a máa sun wó ẹ̀yìn ọlọ́kọ̀ a má sun ejìgbà ìlẹ̀kẹ̀ ̀bá | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìgbésè nla nínú ilé-isé ìgbé sinimá jáde. . . . Àwọn òsèré ti wọ́n lò dara , wọ́n sì kopà ìpín wọ́n dáradára . Wón gbìnyànju . O je àrídájú to dára fun àwọn eré àgbéléwò ti Nàìjíríà. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user @user @user @user @user @user @user @user @user Ògbóǹtarìgì oníṣòwò ẹrú nù un. Obìrin ogun. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nípa ti ìmọ̀ ẹ̀ro, ohùn náà dára púpò, béè sì ni àwòrán yíyà yáàtọ̀ sí ti àtẹ̀yìnwá tí ó sì dára. Wọ́n ṣe àwọn ìran ìjà náà dáradára. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
lẹ́nu kan ṣá ìjọsìn dùn ó tún kọ́ni lọ́gbọ́n ó sì tọ́ni sọ́nà lónìí ẹ̀yin nkọ́ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
3. Ẹ̀rọ ìfọṣọ ni A, ẹ̀rọ ìlọṣọ ni B, ẹ̀rọ gbohùngbohùn ni D, kí ni Ẹ? #Ibeere #Yoruba https://t.co/zW2kSDGKEh | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Owuro l'ojo. """"""""@user: Toò. Ẹ ṣe gírí. Ìgbà ara làá búra."""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ nlẹ́ o ẹ kú àsùnjí ọjọ́ ó múre wá o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Lori Afefe #EruOgo latowo 'Tope Alabi lori eto #OpeSibe latowo Azeez Alujo ati Oduoye Kayode. CC @user @user… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Aago márùn-ún lù, àsìkò tó fún #ibeere #Yoruba. Ta ló lè dáhùn ìbéèrè márùn-ún? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fúnwa ní agbára ìkóraẹniníjàánu kí o sì báwa ṣọ́ ẹnu wa kí a má sọ̀sọkúsọ. Olúwa Ọba ìwọ là nké sí. #adura | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user, e jowo, e ran mi lowo pelu orin ilu ogun. O lo bayi wipe: """"""""Ise ya (2xce), omo ogun, ise ya..."""""""" Ese. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
AKU EWU OSU TITUN o!!! Ninu Osu yi, Idamu koni ya'le wa o Aniku owo, Omo, Ile ati ohun rere gbogbo ni yio je tiwa ninu osu titun yio. ASE!!! https://t.co/Hzx428afzE | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn afibisólóore kan tí a dá lóbìrin, t'ó ní ọmú, ó bímọ àmọ́ tí ò le è fún ọmọ rẹ̀ lọ́mú mu. Kí lọmú ń ṣe láyà bí kì í bá ṣoúnjẹ ọmọ. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Tori akata, l’a fid a yangan, tori eya l’aa ko yanju. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ṣíṣe burúkú àti kíkó radarada. Riiki Hallmark ṣanẹli lè yìí | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ara idi ti mo fi ma n gbadun Bruno Mars niyi """"""""Locked Out of Heaven"""""""" yii dun pupo o kuro ni keremi | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ibi tí à ńlọ là ńwò, a kì í wo ibi tí a ti ṣubú. / We ought to focus on where we are going, not where we had fallen.… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré lásán-làsàn tí kò yẹ kí wọ́n ṣe rárá ni. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
lo gbe konga | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user @user Je ki won mo. #yoruba #bahia #ifa #nigeria | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọ̀rọ̀ ẹnu lágbára ọ̀rọ̀ ni àdúà ọ̀rọ̀ ni èpè ọ̀rọ̀ má ṣe mi ní búburú ṣe mi ní ire | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àlọ àti àbọ̀ wa lónìí dọwọ́ Ọlọ́run. A ò ní kàgbákò o. #adura | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
fàájì rẹpẹtẹ ọjọ́ ẹtì olóyin mọmọ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
16. Mo kí ọ̀ta mo kí òpè ni à ń kí àwọn ọ̀tayò. Báwo la ṣe ń kí aláìsàn? #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Eni a be l'owe! """"""""@user: Òní lòní ń jẹ́! #nigeriavsiran"""""""" | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ kú àjọ̀dùn ọdùn á yabo o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré orí ìtàgé yìí pani leerín gán. . . . Ọmọ!! eré yí jẹ́ eré tó pani l'ẹ́rìn-ín gidi gán. Tí ó bá nwá eré aláwàdà keríkerì eré yí gangan ní kí o mú. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Kò ti ẹ̀ yẹ k'á máa fọ èdè ọ̀gá rárá ni, mo ṣìkejì @user, #PidginEnglish ló yẹ á máa sọ. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Báwo ni wọ́n ṣe mọ̀ wípé èròjà ahóṣùkùṣùkù (floride) àti oje ìtókù ń bẹ nínú igi? Ta ló sọ fún wọn? #LoOrin #Yoruba #Iseselagba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wẹ́ẹ̀tì ẹ̀; olóṣèlú ọmọ ẹgbẹ́ Dẹmọ; DPNC lọ́dún 1960. Ẹgbẹ́ alátakò dáná sun ilé rẹ̀ ní #OkeSokori lágbo-ilé aládìí. #Abeokuta #Nigeria | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bí mo ti ṣe sọ ṣíwájú, oríṣi eégún lówà, lẹ́yìn Ológbojò tó jẹ́ eégún àkọ́kọ́ (àwọn kan gbà pé Ológbojò kò sí nínú eégún) #AraOrunKinkin | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Yorùbá ní, ọmọ tí ó bá ṣípá ni ìyá ẹ̀ ń gbé. Níwọ̀n ìgbà tí ẹ bá ti pinu pé ẹ fẹ́ kọ́ ọ, kò s'éwu lóko àfi gìrì àparò. Mo ṣe tán. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
10.#PariOweYii: Gbangba dẹkùn, kedere bẹ́ẹ̀ wò;... #ibeere #Yoruba #Owe | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
won ti fi igbale gba opolo won lo ni acn oro ode ti fe poju fun awon ara ile won | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọpẹ o dariji atawọn ẹlẹwọn mẹrindinlọgọta | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìgbélárugẹ àṣà #Yoruba ni orin @user #Bolojo, àwọn Gẹ̀lẹ̀dẹ́ #Egbado gan-an ńbẹ nínú fárán orin náà. #Benin https://t.co/gjuHAyv5c4 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Oníròhìn, ilé-iṣẹ́ ìfowópamọ́, àgbèrokobọ́dúndé àti ọ̀kẹ́ àìmọye ènìyàn ní í lò ó láì yọ ilé-ẹ̀kọ́ sílẹ̀. #IAFEE | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
12. Ọ̀rọ̀ onípọ́n-na ni ọ̀rọ̀ tàbí gbólóhùn tí ó ní ju ìtumọ̀ kan lọ, bí àpẹẹrẹ: Jọ - Àpínkẹ́ jọ Adéṣẹwà Ọdún ti jọ (ọdún ti parí) Eṣinṣin ṣù jọ (eeṣin kóra jọ) Fún wa ní àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀ kan. #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn òfin wọ̀nyí mú kí Òronsẹn di ọ̀tá àwọn ìyáálée rẹ̀, wọ́n ń rẹkẹ rẹ̀ torí kò sí ohun tí wọ́n lè ṣe lójú ọkọ wọn. #Igogo | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Adùn ńbẹ lẹ́hìn ewúro. / There is sweetness in bitter-leaf, at the end. [Keep hope alive; it may start out bitter, bu… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọmọ náà ma wà ní ọ̀dọ̀ ẹni tí wọ́n yá ǹkan lọ́wọ́, tí ó ma ma ṣe iṣẹ́ fún wọn. Tí wọ́n kò bá san gbèsè wọn tán, ọmọ náà ò lè kúrò. Kódà, tí onígbèsè bá kú ní àárín ọ̀nà, ọmọ náà ma ṣe iṣẹ́ títí gbèsè náà ma fi pé, kí wọ́n tó da sílẹ̀ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Tan ń rántíi àwọn ìwé Ilésanmí? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ire wọ́ tọ̀ mí wá. Ire pàdé mi níwá, kò mí lẹ́yìn lọ́dún yìí. Orúkọ tuntun, iyì tuntun, aṣọ tuntun, bàtà tuntun."""" #Iwure | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ ṣe prof karin fún àwọn ọ̀rọ̀ ìwúrí ṣeun lọpọlọpọ we are very grateful for your words of insight | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àti pé a ti ń kófìrí wọn ni ìsàlẹ̀-Ọya díẹ̀-díẹ̀. Igi gogoro ń gún wa lójú bọ̀ kọ́un? | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""@user @user Koje tuntun: Olopa Naijeria fe fi ipa gba N25,000 ni Ikeja, owa lori ayalujara. http://t.c… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
aworan awon gomina apc rin ilu maiduguri ni ipade ti wan se ni ilu borno wan ki awon ara ilu wan si se ayewo si htt | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Méjìdínlógún ni àpapọ̀ ẹyọ ilà t'ó wà l'ójú ẹni tó bá ṣá kẹ́kẹ́, mélòó ni àpapọ̀ ẹyọ ilà alábàjà? A. Ọgbọ̀n B. Ogójì D. À… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user @user. Onigba lo pegba lekufo, ki araye to baa fi ko idoti ti a ko ba gbe ede wa ga tani yoo bawa gbeega | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé adébáyọ̀ ògúnlèsì ni ẹni tí ó ni pápákọ̀ òfuurufú nílùú london | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Gbandikan ► firm (mo dúró gbadikan bíi igi ìrókò - I stand firm like the ìrókò tree) #InYoruba #NiYoruba #learnyoruba #koYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
iba lo yẹ ọlọrun ọba ti o ka wa yẹ gẹgẹ bi ọkan alaaye loni ọpẹ lo ye wa oni a san wa o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: B'ọ́mọdé bá ń dalẹ̀, kí ó má ṣe da Ògún; ọ̀rọ̀ Ògún léèwọ̀. #EsinOro🐎 #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òkun #Mediterranean ló là ilẹ̀ yìí àtí #Moroco ní àríwá Afirika. A lè rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àṣà ayálò nínú oúnjẹ, orin, aṣo, ijó, èdè àti ìṣesí wọn. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Dúndùn l'ọsàn ń so, dúndùn l'ọsàn-an wa yóò máa so. Ọ̀ràn adùn kì í tán lọ́rọ̀ oyin, ládùnládùn ni ọ̀rọ̀ wa yóò máa já sí nígbẹ̀yìngbẹ́yín láṣẹ Ọlọ́run Ọba Olódùmarè, nítorí adùn ní í gbẹ́yìn ewúro. #iwure | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kò sí àníàní ìṣẹ̀ṣe làgbà ara ìṣẹ̀ṣe ni a ti ríi kí a tó ó yá a lò ìṣẹ̀ṣe ló bí ìmàle ló tọ́ ọ dàgbà | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Jeki ori e pe ooo ,Ma fo ori e danu nisi 🤣🤣🤣 #9ja #yoruba https://t.co/Ja7wnahOWD | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#TweetYoruba oruko mi ni Otaibayomi-Oluwaobanioje omo Ajibaoye tun mo si Abayomi Ajiboye ni agbole Olukoju nilu Ajowa-Akoko, Ondo. Ire ooo https://t.co/LLKFgmvaC9 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àwọn àgbà ní bí kò bá nídìí obìrin kì í jẹ́ kúmólú ẹṣin ọ̀rọ̀ mìíràn ló tún ní ẹ̀ṣẹ́ kì í dédé ṣẹ́ ò kàn déédéé wáyé | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìbà rẹ Ọlọ́run Ọba. Ọba tó jí wa sáyé lọ́jọ́ òní. Mo júbà rẹ Olódùmarè. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ko mo pe ona jin >RT @user: Parí òwe yìí; ọmọ táa pọ̀n sẹ́yìn; ... #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ki Oba Olojo Eni Ki Ofi Alubarika Si Ise wa. @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kíni à ń pe kiní fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ tí í bo ojú ìkarahun ìgbín bígbìín ò bá rí oúnjẹ jẹ? #Ibeere #Yoruba http://t.co/CdtDIOoUaz | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ese gaani se ado ekiti ni abi ikere | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kí ayé tó di ayé ṣebí ọmọdé kì í wọ aṣọ ìhòhò ọmọlúàbí ni wọ́n ń wà tí wọn yó máa gbé okó àti ìgó kiri ilẹ̀ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user A gbó a tọ́ Perez | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìwòrìọ̀kànràn lodù náà tó sọ sí mi lọ́kàn ẹsẹ̀ odù ifá yìí lọ báyìí ️ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọmọ Nigeria, ìfẹ́ ni k'á máa fi bára wa ṣe, t'ọ̀yàyà, inú kan, tayọ̀tayọ̀ ni k'á máa fi bára wa lò. #OjoOlolufe #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
À rí ìgbọdọ̀ wí, baálé ilé sú 'ápẹ. #EsinOro🐎 #Yoruba https://t.co/anobpLUBqi | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ìyànjú l'àgbẹ̀ ńgbìn, Elédùà nìkan ló mọ b'íṣu ṣe ńta. / Farmers merely sow efforts; God alone knows how the yams are… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nàìjíríà yìí ti gbogbo wa ni... #Nigeria #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
you asked for it now you have it kindly share widely with yorùbá speaking citizens ẹ jẹ́ kí a pawọ́pọ̀ gbógun ti kòkòrò cc | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Modupe lowo Olorun fun ore re la'ye mi @user Mo yọ̀ nínú oreọ̀fẹ́ Olúwa. Ìbẹ̀rù ò sí mọ́. Gbogbo òkè ìṣòro pátápá ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user hmm. Kí Elédùà kówa yọ. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Orin Yorùbá dùn #WorldMusicDay :) | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
A kì í ní ọba méjì nílùú kan, Àfọ̀njá gbéná karí, ìbànújẹ́ gba ọkàn-an rẹ̀ po nítorí ó pàdánù òye Aláàfin, ó di ọ̀tá ọba. #Darandaran | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
*Yoruba adage* Ọsàn tó rí gbajúmọ̀ tí kò bọ́, ẹyẹkẹ́yẹ ni yóò fi jẹ. *_A ripe orange (on an orange tree) that refuses to be plucked by a famous person will get eaten by some strange birds._* Promptly take advantage of opportunities; don't be unduly fussy! #yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Alanu kan to ju egberun lọ. Oluwa jọ ran si mi #Yoruba #SundayMotivation | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó jẹ́ irú ìyàsọ́tọ̀ti àṣà -ìṣèré ti àṣà láti ọ̀dọ̀ àwọn òṣèré fíìmù ti o dide ti Mo fẹ pe a rii diẹ sii. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Òkè òkè lọwọ́ọ ẹní bá ń ṣerú èyí yóó máa lọ, ọ̀rọ̀ yìí ò fẹ́ àdúà. Ẹni mélòó lo ti ta lọ́ọrẹ lásìkòo Kérésì yìí? #Boxingday | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
B'ẹ́nìkan ń yọni lẹ́nu, ẹni à ń yọ lẹ́nu á ní 'ṣé wọ́n bí ṣómi mẹ́ja ni?' @user @user @user @user @user | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé méjìméjì ni àṣẹ ọmọ ẹyẹ tí a ń pè ní ẹyẹlé lóde òní? #BiEyekoSeDiEyele #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìfẹ́ tòótọ́ ló le ṣe é | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òfin ẹrú ò f'àyè gba ẹrú nílé ìjọsìn. Ẹ̀ṣẹ̀ ni láti kọ́ ẹrú l'ẹ́sìn, wọ́n ní adúláwọ̀ kìí ṣ'ọmọ Adámọ̀, Éfà. #RememberSlavery | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ti wan ba jeun yo tan. Wan ma wa bekun bekun kiri @user: Ọlọ́run ò ní ká má jẹun. Ìjẹ wọ̀bìà ni Ọlọ́run ò fọwọ́sí | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìpílẹ̀ ọ̀rọ̀ ìtàn jẹ́ ìyanilẹ́nu díẹ̀ síì ju àwọn pàtó tí ìtàn ìtànjẹ àti akíkanjú yìí, èyítí kò ní ìjìnlẹ̀ ìwà tó pé àti sojúrigindin alayé. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Látorí àṣà 'kú/ẹ kú' tí àwọn ọmọ ìyá wa tó lọ sóko ẹrú nílẹ̀ Amẹ́ríkà ni a fi sọ ìran Yorùbá ní Akú. #ku #oku #eku #aku #ikini #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn Ẹ̀gbá ka ìtakété sókè Ìkòròdú sí ohun àbùkù sí Ẹ̀gbá. Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 1865, Ẹ̀gbá rán Ọmọ ogun ẹgbẹ̀fà (12,000) sí Ìkòròdú, láti pa ìlú náà run. Àwọn ọmọ ogun Ẹ̀gbá rọ̀gbà yí Ìkòròdú ká. Nígbà tí ọ̀rọ̀ yìí dé etí ìgbọ́ ìjọba Britain, wéré ni wọ́n | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
èkàró o gbògbò ēni ti o n kā iwé yi lówó lówó ki òlòrūn kó jē ki ōjō ni san fou wa òlòrun a founwa shé ó yorúba ni iyà mí mó si kó édé yi man làtí kékéré mi mó dūpè gīdī fun òlòrūn | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
aakise faari ese didi si omo adete yoruba proverb translation one does not fancifull | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#EarPod tí #Apple ṣẹ̀ṣẹ̀ gbé jáde yìí bámi létí mu rẹ́gí-rẹ́gí! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
e kaaaro gbogbo omo yoruba a ku isinmi opin ose yii o se daadaa la ji | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo gba níyàn fún àwọn olólùfẹ́ Bàbá Suwe nítorípé kò dára púpọ̀.Sugar Rush wà fún àwọn olólùfẹ́ Bàbá Suwe nìkan. Kò sí íṣe ọnà tó dára, Àwàdà rẹ̀ ṣé ṣọ tẹ́lẹ̀. Kò ní àárò tẹ́lẹ̀ rara. Wọn kò ṣè fún olùwò ọlọ́gbọ́n. Lati ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, iyàrá náà ti kú fún ẹ̀rín láti ìgbà sí ìgbà tó bẹ gẹ ti wọ́n wúkọ́ láì jẹ́ kí wọn m... | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
nǹkan bí ọdún márùnún ni ará ifẹ̀ fi gbé ní ìsóyà ìbàdàn tó dá síi ló mú kí wọ́n ó padà ní | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
tù wọ́n nínú olúwa tù wọ́n nínú àgàn tí kò rọ́mọ gbé pọ̀n tù wọ́n nínú olúwa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
a ti kọ́ ọ̀kan tán a ti bẹ̀rẹ̀ kíkọ ìmíì àwọn ẹ̀dáìtàn inú lítíréṣọ̀ àpilẹ̀kọ tí ó kàn ni ẹ̀ ń wò https | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.