text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
Mo kọ àkọsílẹ̀ tuntun sí http://t.co/M88yO7y9 #yoruba #aworerin | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìkíni. Eré náà ran mi leti ẹkọ kan lati inu iwe geesi kan ti mo ka nígbàtí mo wa níleewe, ti a akọle re je The bottle Imp. Ìtàn eré yii jọmọ ìtàn The bottle imp. Ẹ jo kó sì àríyànjiyàn o, ẹrọ témi nìyẹn. Ẹsẹ. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Òrukò mî ni Òluwà₣èmí mò un fi òrō yí rànšè ni èdè àbíñí mi #TweetInYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
oògùnun ségesège àrùn inú ẹ̀jẹ̀ kànáfùrù osùn ata ìyèré atare a óò da mẹ́rẹ̀ẹ̀rin sínú ọtí ògógóró kí onítọ̀hún ó máa jẹ ẹwà òtílí dáadáa kí ó máa gbo ewée ọkàa bàbà mu ńgbàogbo | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ṣe ayánògbùfọ̀ gbólóhùn inú àwòrán ìsàlẹ̀ yìí fún mi | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ gbọ́ kí la wáyé wá ṣe gan-an? Ṣé iṣẹ́ ojoojúmọ́ náà ni àbí nkan míì wà ń'bẹ̀? #hmmm | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
What do you call this awesome meal in your LOCAL DIALECT? And, what does it go best with? 😀😋 Comment below Kíni ẹ̀ ń pe oúnjẹ aládùn yìí ní Ẹ̀KA ÈDÈ yín? Àti wípé, kíni ẹ fẹ́ràn láti fi tẹ̀ẹ́ lọ sí ìsàlẹ̀ ikùn? 😀😋 Ẹ fi èsì sì ìsàlẹ̀ https://t.co/NwzlxdpH7G | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹni tí à ń gbé ìyàwó bọ̀ wá bá | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Oko baba ẹni kì í tóbi kí ó máà ní ààlà. #EsinOro🐎 #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user @user òrò náà so si mi l'enu o tùn buyo si😊 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹṣeun ó ti yé wa ọ̀rọ̀ pàtàkì lẹ sọ ọlọ́run ọba ò ní padà lẹ́hìn yín o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ariwo. Òkùnkùn. Nàìjíríà. https://t.co/5gg4LGPR5Y | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
búburú irú ti ìwé tí ó dára púpọ̀ | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user Oju wa ò ní fọ́ láṣẹ Èdùmàrè! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ọmọ Jesu ló gbà á o | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user #Fujifilm, iIṣẹ rẹ̀ yàtọ̀ niṣe l'àwòrán rẹ̀ máa n rí kedere | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọlọ́un sì wípé kíyè síi mo fi ewéko gbogbo tó wà lórí ilẹ̀ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìbà adé orí ọba o! Kábíèsí ọba Adédọ̀tun Àrẹ̀mú Gbádébọ̀ III, Aláké Ẹ̀gbá, ẹ kú ọjọ́bìí òní o! """"""""Ẹ̀gbá ọmọ orò tí í dún nọ̀mù. Ọmọ Olúgbọ́njọbí, ọmọ asẹ́ tí í mumi kíkankíkan"""""""". Ẹṣin ọba á jeko pẹ́, ìrùkẹ̀rẹ̀ á sì d'okinni. #Alake #Egba #Abeokuta https://t.co/LiL7PE5ci2 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ilé tí kòkòrò (kan-ni-wọlẹ̀/monimoni) hun fi bo ẹyin rẹ̀, ni a fi ń hun aṣọ olówó iyebíye, sáńyán. #Yoruba https://t.co/Jgt… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
fíìmù yi fi àkókò ṣòfò pátápátá ti o bá si ti ri, jọ̀ọ̀ọ́ má dan wò o | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Lati igbaun, gbogbo AA ti moba tiri, lepa niwon. #Yoruba #2009vs2019 #ARSMCI https://t.co/oSarRBULji | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: 22. kí àwọn sì le máa bá Ọlọ́run sọ̀rọ̀, kí ayé le rọ̀ wọ́n lọ́rùn. @user @user @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀rọ̀ fi 'ni dùgbẹ̀dùgbẹ̀ yin 'ni nù. #Owe #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọmọ ni iyì | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọlọ́run á wo ọlá ààwẹ̀ yìí, á bá wa ká àwọn #BokoHaram lọ́wọ́ kò. Á kó sí wọn nínú. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Otito oro ni se daadaa le wa @user: @user be'e sini awo pele ki ya"""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ihoho la ka ra wa ni gba ti moimoi n shoge lol for yorubas only | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìtàn sọpé #John #Alhponso #d'Aveiro, ọmọ ilẹ̀ẹ #Portugal ló kọ́ ba ẹ̀tí òkun ilúu Ìbíní wọlé ní ǹkan bíi ọdún-un #1485 #Independence | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ogun bẹ́ sílẹ̀, a ti iná bọ ilé, ọ̀gbìn jó mọ́ ilẹ̀ l'óko, àgbà àti ọmọdé kú ikú afináfọnṣu, ìlú di ahoro, koríko gbalẹ̀ padà.#nigbatiwonde | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Iṣẹ́ ńlá ni @user Ìkànnì O'òduà ń ṣe, òǹwòran lè ka ìròhìn lédè Yoòbá. Ó dùn mọ́ mi nínú gan-an gan-an! #Yoruba https://t.co/AD2SIMtO68 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
A lè ní, kò sí ẹni í lo owó ẹyọ mọ́n, a ò le è sọ pé ìwúlò rẹ̀ láwùjọ wa ti lọ. #OwoEyo #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Iba Akoda, Iba Aseda, Iba Oba t'nbe k'aye to wa. Dansaki re Eledu'a""""""""""""""""@user: Mo júbà Ọlọ̀run, mo júbà Olófin Ọ̀run #O… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ó tó ṣe bí òwe o ojú àpá ò lè jọ ojú ara | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Lóòótọ́ àti lododo, kò kúkú sẹ́ni mọ Òkòló nílùú Ọ̀yọ́, kò sẹ́ni mọ apako lásán-làsàn fẹ́ṣin Aláwọ-aàfin. #ItanDowe #Yoruba #Okolo | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Oúnjẹ kì í pẹ́ yán olóúnjẹ lójú, ni ọ̀bọ ṣe fi oúnjẹ tí wọ́n fún un gbo'lẹ̀, á ní """"""""""""""""Kiní burúkú yi tún lè fẹ́ gbàá padà… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wọ́n ní a di ojúu wa, k'á tóó wí k'á tóó fọ̀, ilẹ̀ ti bàjẹ́ :( | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ǹjẹ́, ohun gbogbo t'ó bá ń dùn mí, n ó máa rò f'óríì mi. Oríì mi là mí o, ìwọ lalágbọ̀ràndùn. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fíìmù náà jẹ́ ẹ̀rù láti sọ pé ó kéré jù, láìbìkítà àwọn òṣèré tí ó ga jù lọ. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Eré yìí dùn, o nsọ́ nípa àwọn ọmọ ẹgbẹ́ kan ní Chicago ọ̀kan sìì ti fìgbà kan jẹ́ olórí àwọn ológun ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ọjọ́ márùn-ùn gbáko ni Ọọ̀ni fi ń ṣe ìwúre àti ìbọ fún ọ̀kànlénírinwó irúnmọlẹ̀ (401). #Iseselagba #Olojo #Yoruba #IleIfe | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àṣẹ o àṣẹ n toyin ire gbogbo di ti wa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bẹ́ẹ̀ ni Ọmọ Ọba ... Ìwá ẹni ni àwúre ẹni #Orunmila http://t.co/3NuBo61j4M | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
irú adé wo ni akoro oríkògbófo | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ese kọ́ l'ọmọdé àkọ́kọ́ t'áwọn bíi Yinusa ńfi s'ábẹ́. Òfin'lẹ̀ wa f'àyè gbàgbàkugbà, ara ìwà pálapàla tía kọ́ #Nigbatiwonde nù n. #FreeEse | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ko s’ohun ti mo mu wa, Mo rọ̀ mọ agbelebu; Mo wa k’od’asọ̀ bo mi, Mo nwo Ọ fún iranwọ; Mo wà sib’orisun ní, Wẹ mí, Olu… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ogbe orí àkùkọ, kì í ṣe mímọ̀ ọ́n ṣe àkùkọ; Elédùà ló dá àkùkọ lọ́lá. / The comb on the cock's head is not of its own making; it is the blessing of God. [Be modest and thankful; our endowments much more reflect God's favour on us than our efforts.] #Yoruba #proverb | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èso wọ́ sílẹ̀ pòròpórò, afẹ́fẹ́ ń fẹ́___. #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwé, jẹ́ k'ọ́ mọ̀ wípé ìjàmbá ọkọ̀ dánfó ló fa súnkẹrẹ fàkẹrẹ ní kété tí a bá kúrò ní Adéníji, bí a bá ń lọ Òwòrò. #3RDMB @user 🚌 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kara ole o... Oluwu tese Jeje ... proud #Yoruba https://t.co/BDsGpFAqnW | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ǹjẹ́ ìwọ mọ̀ wípé ní ọdún-un 1884, àwọn ogúnlémdé 50, 000 – 60, 000 tí í ṣe ọmọ Ìbàdàn/Ọ̀yọ́ ló ń gbé ní Modákẹ́kẹ́? #IfeModakeke. #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""""""""""@user: ♫ Orí mi tètè là kórí ọlọ́rọ̀ má pè ẹ́ rán níṣe ♫ @user"""""""""""""""" Ire o! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bí mo ti ṣe wí ní ṣàájú pé, onírúurú ibi ní à ńkọ ilà sí lára, bí a ṣe ńkọ ilà kan sápá, là ńkọ òmíràn sí àyà #ila #yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user naija le ri yen. Won oni se, won osi ni je ni o'se se. Afe a'je maje a yo ni won. Awon ojelu wonwon yen. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Tunde Kelani ( @user ), e ku ayajo ojo ibi yin o. Olorun yio tubo maa fun yin l'okun ati agbara. Happy birthday, sir. ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àsé ijó be lésè àwon """"""""super-excited-to-discuss-with-google's-CEO"""""""" náà #TweetInYoruba https://t.co/5mRSCKqOgq | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
bákan náà ni àwọn ọlọ́sanyìn ṣe máa ń gbọ́ ohùn onírúurú ewé tí yóò ṣe ìwòsàn fún ọmọ aráyé | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Abala #ibeere #Yoruba ni ọpọ́n súnkàn. Ta ń mọ̀ ọ́n? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
... ọkọ́-ńlọ/ọkọ́-ńbọ̀, òjò-má-petí, olówu dúdú, máforíbalẹ̀(f'ọ́kọ) àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. #AwaLaNiIrun #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àsọdùn kọ́ rárá ni wípé ọbẹ̀ tí a fi ìṣasùn sè ládùn ju èyí tí a fi irin fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ sè lọ. Bírọ́ ni, ẹ já mi. #Iseselagba #emafiwe #Yoruba https://t.co/VGTllj98oE | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
7. Yàtọ̀ sí ìbẹ́ta, orúkọ àmútọ̀runwá wo ni à ń pe ọmọ mẹ́ta tí a bí papọ̀? #Ibeere #Yoruba #learnyoruba #language #speakyoruba #MotherTongueDay https://t.co/Al48MtWRYS | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré Naijiria tó dára jù láti bi ọdún mẹwa sẹ́yìn.. . Ni lóòótọ́, eré yii mu àwọn ìrírí òun to ti ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ tó ti pé wá. Eléyìí jẹ́ eré tó tayọ to jáde wá láti Nàìjíríà lati bi ọdún mẹwa sẹ́yìn. Ó yàtò si eré àgbéléwò àwọn ọjọ́ tó ti pé. Banky W kú isé, o tayọ. Mi o kin wo eré ti Naijiria tẹ́lẹ̀ torí ìṣekúṣe tí won m... | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: @user amin ooo atemi ati ebi mi oo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìyá ni wúrà iyebíye ìyá tí a kò lè fowó rà | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀bún ríkú ọkọ dìrọ̀ mọ́n. #EsinOro #Yoruba @user #June12 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Amin ati emi na | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ jẹ́ á tọ́jú àwọn ògo wẹrẹ wa torí àwọn ni eérú bí iná wa bá kú àwọn ni ọ̀gẹ̀dẹ̀ tí yóò rọ́pò wa bí a bá papòdà | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ̀yin ọ̀dọ́ àwa lòpó múléró ìlọsíwájú ìdàgbàsókè ìlú wa ń bẹ lọ́wọ́ èmi àti ìwọ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: MRD = mo rẹrin dákú | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí n ba níbẹ̀ lá sán, inú ojúu rẹ̀ ni ń wò tààrà ... | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
òótọ́ ni wọ́n á ní ọba ò gúnwà wọ́n a gbé igbá lé e lọ́wọ́ hmm | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ọjọ́ kan pẹ̀lú o baba awo. Bóo ni nkan? | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ̀là òwú kì í rí olóko kí ó di ojú mọ́ orí. #EsinOro🐎 #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn aláwàdà wọ̀nyí ò kúkú pani l'ẹ́rìn-ín o jàre. Àfi kí wọ́n máa fi àwọn èèyàn ṣe yẹ̀yẹ́ ṣá. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kpali' kòní nkàankan.eré orí-ìtàgé tíkò múná dóko, òfìfo ní 'Kpali' jẹ́ ìtàn tí kòní ìtumọ̀ ní síso | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ba bá ní 'Lágbájá fi kàsádà l'ágbọn' ó túmọ̀ sí wípé èèyàn/Lágbájá wọ bàbá kò bá màmá tan aṣọ; èyí ni aṣọ tí ò bára wọn mu. #Idahun #Ibeere | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: @user : itumo owe ni wipe a ko gbodo je afara si nkan ti a ba se(not to procrastinate)"""" #ibeere #yooba #owe | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré náà kò pé ṣùgbọn ìyàlẹ̣́nu ni ó jẹ̣́ | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ajé Olùpèsè ọrọ̀ kú ojúmọ́ o! Ajé ìwọ làjíkí, ìwọ làjíkẹ̀, ìwọ làjípè. Ìwọ ni mo mú ṣ'okùn. Ajé ìwọ ni mo mú ṣ'edẹ. Ìwọ ní í fi ẹni iwájú sílẹ̀ ṣe t'ẹ̀yìn lóore. Ajé ṣe mí lóore ọlá, ọlà àti arísìkí ọrọ̀, sọ mí d'Ajífọwọ́bajé. #iwure #OjoAje #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Ka sun ka se bi eni ku, Ka wo eniti o daro eni.... #Yoruba #yooba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ṣé ẹlòmíràn gbà pẹ̀lú mi wípé ohun tí wọn fi síwájú kàn dàbí àgbélébùú láàrín Àǹtónì Mákì àti Dáníẹ́lì Kàlúyà ni? | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
inú mi dùn mo jí sáyé mo jí sáyọ̀ mo jí síre èdùà kú iṣẹ́ ìyanu o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
eléyìí sún mọ dáada | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ẹ ṣe àlàyé díẹ̀ lórí rẹ̀ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
5. Àfòmọ́ ìbẹ̀rẹ̀ |a| àti mọ́fìmù àdádúró |lọ| ni a fi ṣẹ̀dá |àlọ|, ṣẹ̀dá gbólóhùn mìíràn pẹ̀lú |a| àti |lọ|. #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#Repost @user with @user ・・・ A ó máa retí àwọn ìbéèrè yín o... . . . . . . . . . . . . . #yoruba #BBCNewsYoruba @user https://t.co/xNsFkhllKf | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
8 » Wọn kì í gbé wọọ́n sin. #Eegun #Yoruba #Oyeku | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Dánfó gbókìtì lórí afárá #3RDMB bí a bá ń lọ #Oworo, súnkẹrẹfàkẹrẹ ti bẹ̀rẹ̀ torí ìran @user @user http://t.co/wyCxYAn0Wi | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ẹ KÚ ÀÁRỌ̀ O... 😍 AÀ JÍIRE BÍ? 🤷♀️ ÈDÙMÀRÈ Á PA ÀLỌ ÀTI ÀBỌ̀ YÍN MỌ́ LỌ́SẸ̀ YÍ. ỌWỌ́ YÍN Ò NÍÍ KAN ÌSÀLẸ̀ ÀPÒ. TÁBÌLÌ YÍN YÓ… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
What city do they eulogize as: Ìlú wo ni à ń kì ní: Òjò pa Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀, ọmọ Àtìbà. Níbi tí wọ́n ti ní kí olówó ó gb'owó, kí Ìwọ̀fà ó da ti ọwọ́ rẹ̀ sílẹ̀. Ṣèbí kí ó lè bà di ìjà, kó lè bà di ápọn ni. Kí ọba aládé ó le r'íhun jẹ ni? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ rí kiní gíga tó dà bíi òkè yìí à bẹ́ ò ríi ọ̀pọ̀ ló gbabẹ̀ bá ọba lọ ìrìnàjò àrìnmabọ̀ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#Yoruba Eko eleko Oun ni Egba elegba. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọ̀rúnmìlà fi ifá kọ́ ọmọ rẹ̀ àwọn ọmọ ẹdú wọ̀nyí ló pín ìmọ̀ ifá kárí ayé | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Kò tọ́pẹ́ o! ṣé ẹ nkọ́ Yoruba ni? Mo rí i pé ẹ kìí ṣe ọmọ Naija :) | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó yàn Yorùbá gẹ́gẹ́ bíi minisita fún ètò isuna, minisita fún ilé ìgbé àti iná monamona, minisita fún eto ìlera, minisita fún ọ̀rọ̀ to ń lọ, minisita fún ibanisoro,"""" | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fàdákà ni o. Fatma Omar fi àgbà hàn án. Àmọ́ ó gbìyànjú púpọ̀ púpọ̀!! #TeamNigeria #Paralympics | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
a kú jímọ̀ olóyin o fàájì ìsimi bẹ̀rẹ̀ ni pẹrẹwu | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user @user Mo rín ẹ̀rín tàkìtì. Ẹ̀bùn gidi ni Ọlọ́run fún ọ̀gbẹ́ni @user yìí ṣá o! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
si ẹyin alatileyin buhari a rọ yín láti gbaju mọ àṣeyọrí àti ifomoniyanse oludije ẹ̀rí láti sá fihan fún ifesunkani láti ilè okere kii ṣe ọ̀rọ̀ àbùkù | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Àgbàdo inú ìgò, ó di àwòmọ́jú fún adìyẹ. / The corns in a bottle are viewed with disdain by the hen. [People are wont… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ǹjẹ́ ẹ mọ orúkọ ẹyẹ tí àwọn òyìnbò ń pè Guinea Fowl? Ẹ bá wa kọọ́ ní Yòrùbá. #atelewo #àtélewó #yoruba #yorubaculture #edeyoruba #nigerianculture #africanculture #yorubanimi #africanculture #animallove #poultry #agric https://t.co/fm2AV6nEHM | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.