text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
@user: @user oro loso omoyoba, ejire abi ejirebi"""" Ojúmọ́ 're ni :) #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ọ̀rọ̀ tó máa di akàn, bí ẹja ni í kọ́kọ́ máa ńrí. / What will turn out well at the end, often starts out as unpleasan…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wí pé èso kan náà tí a ń pè ní 'ìbẹ́pe' ní orúkọ mìíìn tí a tún ń pè é? Bí o bá fẹ́ yàgbẹ́ wọ́ọ́rọ́wọ́, jẹ ṣi…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bákannáà, @user àti @user sọ ipa tí ilé-iṣẹ́ àwọn ń kó ní ti ẹ̀kọ́ oríi ẹ̀rọ-ayárabíàṣá #SMWBetterEdu http://t.co/SbVkatIpiQ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bẹ́ẹ̀sì ni 'igi gbígbẹ ò ṣe é tẹ̀ ní kọ̀ngọ̀' #yoruba #owe #proverb #ISupportBreastCancerAwareness
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Isọ itan ti ko dara pupọ… ati atunkọ itan-akọọlẹ pupọ nitori ìtàn fiimu naa
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
èdè yorùbá dùn gbongbon kan sii ènìyàn àtàtà ni eya yorùbá jé wọn máa ń kó ènìyàn mọ́ra wọn sì nifẹ sí ibagbepo àlà
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ṣé òótọ́ ni pé kúnlé ti lọ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìwọ ikú òpònú abaradúdú wọ, o ò ṣe é 're o. O d'óró, o ṣ'èkà, o m'ẹ́ni rere lọ. @user ṣe bẹ́ẹ̀ ó lọ.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ajé á wá wa wá o!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
2. Nígbà àtijọ́, níbo ni àwọn ọkùnrin máa ń lọ láti wá aya, tí àwọn obìrin ti máa ń rí ọkọ? A) Ọjà B) Odò D) Ilé ìjọsìn #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹgbọ́n wa. Ṣé ẹ nlọ sí #smwMotherTongue ?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eso pele lo ye ka se aiye gba jeje baba obey commander e si ku dede iwo yi oto ojo meta
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Gẹ́gẹ́ bí àpẹẹrẹ: Ọmú-u Fúnmilọ́lá, kì í ṣe ọmú Fúnmilọ́lá. Okó-o Kọ́láwọlé ✔️ Okó Kọ́láwọlé ❌ Bàtà-à mi ✔️ Bàtà mi ❌ Ir…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user: Èmi ò f'ẹ̀ẹ̀kan kọbiara sí ọ̀rọ̀ olóṣèlú #Naija o jàre. Gbogbo ẹ̀ ò kúkú yémi tẹ́lẹ̀. #pdp #acn #GEJ atbbl"""" hmmm Ẹ rí i ṣọ!
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: 1. Akìí sọfún àgbà pé ojú ẹ̀ jìn; ìrírí tí àgbàlagbà tirí lójẹ́ kí ojú ẹ̀ jìn. @user @user @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user àwọn Àjàyí àti CMS náà ló kọ̀yìn sí àwọn àṣà tòun ìṣe yìí, wọ́n ní kò dáa, irinṣẹ́ Èṣú ni wọ́n pè é fún wa.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ki ifisowo eri lori ise to le niye o gbudo niye ninu owo koto le niye lori owo o gbudo le sese lati fi ranse lori ero ayelujara to tobi gidigan fun apere ona lati do ero ranse lori ayelujare bi
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
sí ibẹ̀, kí ó kú, lẹ́hìn tí wọ́n ti gé ara rẹ̀ bàjẹ́. Ṣùgbọ́n, ó yè, ó sì wọ́ lọ sí inú igbó. Ó tiraka láti wà láyé, tí ó sì yè lórí jíjẹ èso nínú igbó. Lẹ́hìn ti ara rẹ̀ ṣe gírí, ó di àgbẹ̀ Àyè ṣí sílẹ̀ fún láti pàdé àwọn èèyàn kan nínú abúlé kan Gẹ́gẹ́ bíi
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user @user O le te obirin lorun 😣 #TwitterYoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn Yoòbá ní orúkọ tí wọ́n ń pe ọjọ́ kí àyípadà ìgbàlódé tóó fọ́ gbogbo rẹ̀ lójú poo. #OjoIsinmi #Yoruba #Itan
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
amin aase waa ose tuntun yoo san wa si owo somo si aiku baale oro
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
1] Kíni orúkọ tí à ń pe àga yìí? 2] Pa òwe kan tó jẹ mọ́ àga yìí. #Ibeere #YorubaQnA http://t.co/BgkL7zNPyx
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
4. A gbé ìyàwó nígbà òjò, ó ní kí a máà f'ọwọ́ kan ìdí òun. Kí ni o? #Ibeere #Yoruba #Alo #Apamo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
alagbala imole alafin orun alase orun atobi loye
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọ̀rọ̀ àpọ́nlé adverb it is a word that modifies a verb adjective in a sentence ìdòwú sá lọ ráúráú ìdòwú runs off completely eré náà tètè tàán the race finished too quickly igi ìrókò náà ga gogoro the ìrókò tree is very tall
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
it is igi ọsàn
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
e joowo booni e seun fi ami si awon oro yin pátákóìkọ̀wé ni
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Lẹ́ẹ̀kan si, ẹni tó gbé eré yi jáde sìnà. . Eré náà kò dá lé oun kan pàto, ó kan jálu ara wọn
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Fífi àlejò sí ìyára tàbí ibi tí yóò forí lélẹ̀ sùn sí ni à ń pè ní 'SÍSỌ LỌ́JỌ̀'. Fún àpẹẹrẹ, bí mo bá ní """"""""nígbà tí mo lọ kí @user, babá sọ mí ní ọjọ̀"""""""", ohun tí mò ń sọ ni wípé, Ọọ̀ní fún mi níyàrá tí mo dé sí. #IrinisiNiIsoniNiOjo #Yoruba #Alaye
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọ̀rọ̀ìperí wo ni fún athlete lédè yorùbá
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: #IkiniFriday mo ki @user @user @user @user eku ise igbe ede ati asa ise ile wa laruge.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Aseyi Samodun Baba. Odunpe Odunjo, Amodun wa Esin pe..Ase O! (Irosun Meji)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
"Father of Today" tí lọ tààrà jù láti wá sí sinima. Kì Í ṣe pé kò dára láti wò, ṣùgbọ́n ó ti lọ tààrà jù. Gbogbo ohun tó wà nínú "Father of Today" jé̩ gbèdéke kékeré tí eré yẹ̩ kí o ní. Eré naa fihan pé àwo̩n tó ṣe é kí í ṣe akós̩é̩mo̩sé̩ òs̩èré.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
A kú ọrọ̀ ajé ònìí o. Mo lérò wípé ajé bu igbá yín jẹ?
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
olojo ibi ijo kan e o e mi e a se pupo kaye wa gbo wa to wa fi erigi je obi amin ab
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bẹ́ẹ̀ná ni fáàrí àṣejù. wọ́n ní oko olówó ní í múni lọ. #ogbon #yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user @user Iro ponbele ni eyi. Agbajowo ni oro to wa nile yi. Ise Awodi ko da ise A…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Láyé àtijọ́, àwọn àwòràwọ̀ í ma á na ọ̀pá àṣẹ sí ọwọ́ ẹni, wọ́n á ki Ifá, kedere sì ni ohun gbogbo nípa ẹnítọ̀hún yóò hàn.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn òsèré jẹ́ ńlá, ṣùgbọ́n àwọn àpéjọ eré kò lágbára.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Aàrẹ ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́. Ta ló ń wò ó? @user #DemocracyDay
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ǹjẹ́ ẹ ti gbọ́ wí pé bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ wọ ilé ẹ̀kọ́ ifásitì àti gbogbonìṣe ní ìpínlẹ̀ yìí onítọ̀hún gbọ́dọ̀ ní èdè yorùbá ńnú àwọn ẹ̀kọ́ ìgbaniwọlé
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ̀lúkú jẹ́ irúfẹ́ orò àwọn ọmọ ìlú Ìkòròdú. Àwọn ni ọmọ afèlè méjì jà. #idahun #Ibeere #Yoruba #learnyoruba https://t.co/1Cn295bTz6
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
abi kayefi gbaa nje eniyan a wa maa ru eru eleru ko fa tie lowo ni
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Okan lara awon ere Nolliwodu ti o peregede lati bi odun mewa seyin.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
8. Gbólóhùn mìíràn fún òpònú ni akídanidání, òmùgọ̀, èdì dàrẹ́, dàdańdìdì, _______, _________ #Ibeere #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
13.Ewì alohùn ni Rárà, Ẹkún-ìyàwó,___, òkú pípè àti___? #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eyin ọdọ naijiria nigbati a ba sọrọ pẹlu ohun kan ti fi imo ṣọkan a le koju ohunkohun ni ọna wa a le fi opin si ebi a
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eba takiti ki e forisole jega ati o gbe se ran yin ti e ba se radarada yin tan ni ss ati se lo nibo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Lord, please remove àwon afojú féni ma fokàn féni àti àwon tí wón se ìbàjè mi from my life🙏 #olakemisdiary #yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Egbe agbaboolu #barcelona fi di remi lale ana ni idije #Spanish #laliga #EdeYorubaDunLeti #yoruba #yorubanimi #yorubaculture #photo @user Somewhere in Nigeria https://t.co/vbdLu3kcXv
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù wo ló ma gbé kan ṣánlẹ̀ nígbàtí bá gbéná wo ojú man city lónìí |
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user. Koni gbe awa ati ebi, ara ati ore lo oo. Ojo atura lo ma je fun wa. Ase Edumare.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
isele ti o tin sele ni orile ede wa paapaa ni agbegbe awon awusa o fe dabi pe a tin di orile ede lo die die
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Dokita Lanre jẹ ìyípadà tó dùn moní.. . Inu mi dun wipe mo wà lára àwọn ti o kọkọ wá nínú reluwe eré yii. Ìyípadà ti o dun mo ni ni o jẹ. Ìtàn na ni ìpìlẹ ti o dára tí wọn sì gbé jade dáadáa nipasẹ ìkópa awọn òṣèré ti o kún oju oṣuwọn.. . Eré tó yẹ fún wíwò.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ní ìgbà ẹrú ní Ìbàdàn, àwọn ẹrú ọkùnrin tó dáńgájíá nílẹ̀, ni wọn ma kọ́ ní ọ̀nà ogun jíjà. Kò sí gbọdọ̀ wáyé wípé, ẹnikẹ́ni ma ta ọ̀kan nínú àwọn ẹrú ológun yìí, báhú kó ti lé wù kó rí. Àwọn ẹrú ológun wọ̀nyìí yóò di ọmọ ilé pátápátá ni.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọjọ́ ajé di dídé bí ewé adé ọlọ́run ọba dé wa ládé aláfíà
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ara le koko bí ògún àgbẹ̀dẹ. Ẹ kú àmójúbà wa :) Òtútù ló kàn pọ̀ díẹ̀ o.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
òní ló kù fún a óò làájá koko lọ́lá elédùà
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
oko ẹbí tí yóò máa pèsè oúnjẹ pẹ́ẹ̀pẹ̀ẹ̀pẹ́ fún ilé tí a sì lè tà níbẹ̀ ni ọ̀nà àbáyọ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user Ọba àwọn ọba. Adàgbàmápààrọ̀oyè. Olódùmrè Ọba ìyè.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Abala ke̟è̟é̟dógún. E̟nì kò̟ò̟kan ló ní è̟tó̟ láti jé̟ o̟mo̟ orílè̟-èdè kan. A kò lè s̟àdédé gba è̟tó̟ jíjé̟ o̟mo̟ orílè̟-èdè e̟ni ló̟wó̟ e̟nìké̟ni láìnídìí tàbí kí a kò̟ fún e̟nìké̟ni láti yàn láti jé̟ o̟mo̟ orílè̟-èdè mìíràn.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àjẹbánu ìjẹẹ̀wẹ̀hìn wọ̀nbílíkíwọ̀bìà ọ̀kánjúà olè ayé ìsẹhín ni ò jẹ́ káyé ó rójú
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user A dupe pe opin Ose de. Iyen ja si isimi fun wa.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kódà ó tutù nini tó jẹ́ pé n kò rí oun tí mo fẹ́ fi wé ńṣe ni mo dìkáká dìkuku bíi baba sùwé
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ kú ìrọ̀lẹ́ o ẹ̀yin tèmi ṣé ká ṣeré kan
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ekuru ati Obe Gbegiri RT @user: Yàtọ̀ sí àkàrà, sọ oúnjẹ méjì tí a fi ẹ̀wà ṣe #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọ Ìkálẹ̀ máa gbọ́ #AgbeOmoIkale lóríi @user pẹ̀lú Fápohùndà. Àbí lórí ayélujára https://t.co/G9TeDTUowG #OnAir #1049SMAFM
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ta ló máa wọlé? #Buhari àbí #Jonathan ?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
4. Ìbírọ̀gbà-á yáyo ọkàn ju Kílàńkó lọ. Kí ni gbólóhùn òmíràn fún àkànlò èdè 'yáyo ọkàn'? A. Ìgboyà B. Ìtẹ́lọ́rùn D. Ìtẹríba #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo ba @user yo Ayo ojo ibi o, emi a se pupo e laye, igba ile a lesi, awo ile a le si, aseyi seemii, lase Edumare
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ki Olohun yan fun wa #tweetinyoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ̀sìn ìgbàlódé ti gba àṣàa danù lọ́wọ́ọ wa gbáà, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ kan ò bá máà ti w'áyé. Bíi ìwà àfọọ́rá. #OwoFunOle #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Tọ́rọ́ àti kọ́bọ̀ tí a bá pa yìí lè di ọrọ̀ bí a bá mú òwò ọ̀hún lóòkúnkúndún.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Kokoro naa nko? A ko rii mo loode oni RT @user: Àádùn náà nbẹ. #ounjeYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ KÚ OJÚMỌ́... 😍 GBOGBO ÀWỌN ARÁ-ILÉ ŃKỌ́? 🤷‍♀️ Ọ̀SẸ̀ YÍ Á TÙ WÁ LÁRA LÁṢẸ ÈDÙMÀRÈ! 🙏 (Good morning... How's the family? May this week be favourable to you by God's grace!) #yoruba #iwure #adura #ojumoire #ekaaro… https://t.co/FFhHpdQvjT
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo lo si odo iya agba lonii, Mama se adura enu feree bo Inu mi dun gaan
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọjọ́ kẹ́ta ẹ̀ta ǹ tagbá ọjọ́ ajé oṣù kẹ́ta ọdún mẹ́tamẹ́ta ni ìbùkún wa yóò jẹ́ lọ́sẹ̀ yìí àti oṣù yìí
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
osise ijoba ni mi igba miran mo ma n je constituted osise ofisi olori osi
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn ẹlòmìíràn ò mọ nípa owó àtijọ́ tí a mọ̀ sí #OwoEyo. Lónìí ni a óò tú pẹẹrẹpẹ́ẹ̀rẹ̀ nípa owó yìí. #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ó ní àwọn ẹranko tí kò sí ní apá ọ̀dọ̀ wa níbí ó sì ní àwọn ẹranko tí a ní níbí tí kò sí ńbòmíràn bẹ́ẹ̀ làwọn ewéko náà béranko ẹlẹ́jẹ̀ tútù ṣe wà ni ẹranko ẹlẹ́jẹ̀ gbígbóná ẹranko ẹlẹ́jẹ̀ tútù ni ẹranko tí wọ́n ń pè ní tiger kò sí níbí ẹkùn
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Jedi ko m'akowe...#ATUNTE! """"""""""""""""@user: Pápàpá iṣẹ́ tòní ń tán lọ. Ó wá ku fàájì pẹrẹhu. Àríyá kẹlẹlẹ.""""""""""""""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user @user @user Nkan ti e hun so fun wa nipe kii awa omo Yoruba f'ipa ta ip…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Sin ► hide/conceal; (ó sín owó sóké àjà - he concealed money on top of the ceiling) #InYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
se o mo pe ofin apapo ile naijiria nikan ko ni ofin ti a ni sugbon ohun ni ofin ti o ga julo ti awon ofin yoku wa labe ready awon ofin miran wa won da won fun orisirisi nkan and fun awon eka ijoba ti o da won
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ogunde - Yoruba E Ronu. Akoko yii gan ni o ye ki a ronu o! - YouTube https://t.co/xBMLP8MKzi @user @user @user…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
adúpẹ ọba òkè pé owó ti pe many thanks to god the donation is met
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
YORUBA: Owó ti ò sí jẹ̀dí jẹ̀dí kan ò lè gbá. ENGLISH: No degree of pile ailment can cause one to spend what one does not have. #LearnYorubaToEnglish #Yoruba #Proverbs #English #Oluwadarmie
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ẹ jẹ́ k'á ṣeré ọpọlọ. #Ibeere #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Àyájọ́ ọjọ́ oyin àgbáyé 🐝 #WorldBeeDay
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àṣeyọrí ńlá ni ẹ̀san tó dára jù frank sinatra
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Swallow yanjú ọ̀pọ̀lọpọ̀ wàhálà àwùjọ léréfèé.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user Ki lo ti ri? Kese kese lo ti ri, kasa kasa nbo, baba kese kese. I hope you get a good #Yoruba translator. Wonders shall not end.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Tí a bá fi AWỌ ÌLÙ ráńṣẹ́, a fi ń pa àrọko wípé, àṣírí tó wà láàárín àwọn méjèèjì, ò gbọ́dọ̀ tù ú sí ìta
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Haruna Ishola, baba gani agba wipe; Awon odale ti gun igi rekorja ewe. https://t.co/ErIyblnKQd
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìtàn àtọwọ́dọwọ́ kan sọ pé kí Ṣọ̀ún tó jẹ́ ọba Ògbómọ̀ṣọ́ ... #Ogbomoso
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
onise iyanumiracle worker onise arawonderful onise nlagreat god mimo mimo mimoholy holy holy oba to ninu mimorighteous god oba alaya funfunimmaculate god not gonna lie praising god in sounds a lot more fun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí ó fi aro sí ẹsẹ̀ Wọ́n ní á ṣe abiyamọ Yewájobí ṣe bẹ́ẹ̀ ló yá Ó bẹ̀rẹ̀ sí í bímọ #Gelede #Yoruba #Ifa #Odu #IworiMeji
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mi ò rántí sọ pé a kì í fi òóró ẹ̀pà, ewé dín róbó, òróró tí ó sun jáde lára ẹ̀gúsí nígbà tí a yan án lóríi iná ni a óò fi dín in. Ṣó yé?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Yoruba omo Karo O ji ire! Eje ki a ronu jinle o! Ose wa je wipe igba ti Aare GEJ fe bere ipolongo ibo ni #BokoHaram wa gbo oro si lenu?
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train