text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
Lótìítọ́ àti lódodo, a ti kọjá àsìkò tí ó yẹ kí èèyàn kàn máa kọ ọ̀rọ̀ Yorùbá lásán láìfi àmì ohùn si. Ẹ jẹ́ a dẹ́kun àti máa ṣi àwọn Òǹkàwé lọ́nà. You can add the new feather """"""""""""""""Yorùbá Tonal Mark Activist"""""""""""""""" to my cap😊 #yorubarevolution #tonalsound #yorubarules #yoruba https://t.co/dtIxOPXau... | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ti ran iko nise osun osogbo, rere ni osun fun mi oroki onile obi, alaro omo asala EDUMARE BAWA DA ILU OSOSGBO SI ASE? https://t.co/DSK1YuaK1h | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Awọn igbesẹ ipilẹ atí ilana lati gbe awọn ọja ati iṣẹ jade kuro ni Nàìjíríà labẹ AfCFTA https://t.co/lv0RS7En0f #Oja #Itaja #Africa #Nigeria #NOTN #BusinessReady #Competitiveness #OneCommonMarket #Yoruba Version #WaZoBia | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""@user: Ah, mo'ba yin yo o!""""""""@user: Óyá mó ti dá'mi sí wájú, kí ng wá máa tẹ'lẹ̀ tútù."""""""""""""""" Nitemi, mo ba ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Eni lo bo ola loju ki ariya to ma san ni repete. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ara àntí ò yá Ara àntí ò yá Ìkọ́kọrẹ́ ń wọlé, abọ́ ń jáde. This should cure my body ache 🤔 🤔 Ọmọ #Ìjẹ̀bú èmi n wà https://t.co/j3BQLqXObk | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Tí ẹyin adìyẹ ò bá fọ́, oromọadìyẹ ò leè wáyé. / If the chicken's (incubated) egg did not crack, the chick could not have been hatched. [Adversity may well be a stepping stone; keep hope alive.] #Yoruba #proverb | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
E ku isinmi opin ose yii o se daadaa le wa @user @user @user @user @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
orí lànà fún wa ká sún kẹ́rẹ́ dowó ká sún kẹ̀rẹ̀ dọlá owó tútù àbùùbùtán owó àdójúti àgbàná èyí mo ṣe ládùúà fún gbogbo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
New slang : Shey o n whine mi ni #Yoruba #Africa ♤ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ jẹ́ gbàdúrà kí omíyalé yalé àwọn #Bokoharam kí omi ya síbi tí wọ́n kó ìbọn pamọ́ sí kó ba gbogbo àdó olóró wọn jẹ́ ;) | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀la dé tán, ojú wa lá ṣe #NigeriaDecides2015 #ibo2015 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user @user @user Ẹ kú ìdánilẹ́kọ̀ọ́ yìí. Ó ga jù. Ọlọ́ru tó dá èdè ọ̀hún kò ní pa á rẹ́ mọ́n wa lẹ́nu o. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
160 - Ọgọ́jọ 170 - Àádọ́sàán 180 - Ọgọ́sàán 190 - Ẹ́wàádínígba 200 - Igba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: àyànmọ́ je ohun ti a yan m'oni lati ode orun, idi niyi ti a fi nso wipe """"""""ori lelejo'""""""""RT @user: Bí wọ́n bá tún ní 'ày… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
KI ARA DE MI DEDE L'ODUN TUNTUN http://t.co/62s9A3m5 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
.'Ajímọ̀bi' ò kọ ti àánú; ẹni orí bá rán sí'ni l'ó ń ṣe 'ni lóore. #Oyo #AtunpaOwe #Yoruba @user @user @user | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Oṣù kẹwàá ọdún la lò tán yìí. A dúpẹ́ Ọlọ́run. Oṣù tí ń bọ̀, Ọba lókè jẹ́ kó yẹ wá o. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ire Olókùn Ajíbájé, máa bọ̀ lọ́dọ̀ọ̀ mi tààrà sòsé, nítorí mo ní ohun rere láti fi ọ́ ṣe. K'ó rí bẹ́ẹ̀, kí ó ṣẹ bẹ́ẹ̀. #iwure | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ní agbára, ṣùgbọ́n ó kùnà láti fà ọ́ wọlé | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user Olúwa à jẹ ki wọn pẹ, ki wọn jẹ oúnjẹ ọmọ pẹ pẹ pẹ bi obi ṣe n pẹ lẹnú | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ẹnu tó bá ti jẹ dòdò, kò ní lè sọ òdodo. / The mouth that has been compromised with sweet things can hardly speak the… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
N ó dé'bẹ̀ lọ́jọ́ kan b'Ólúwa bá fẹ́. Ilé ìmọ̀, ibi t'áàgbáyé ti wá ń gb'ẹ̀kọ́ àti ìwé tó kún fún òtítọ́. #Timbuktu | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ata jere oja fun gbogbo awa onisowo leni ooo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user Kú iṣẹ́ ribiribi, orí ẹ á kànkè! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹyin ọmọ kaarọ ojire ẹ ku ojumọ o ojumọ ayọ ni yo jẹ fun gbogbo wa o àmín rt ẹkú ojúmọ́ o ṣé dáadáa l | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#YorubaTwitter Ẹ jọ̀wọ́ mo nílò ìrànlọ́wọ́ yín. I need links to Corona related songs,poems in Yorùbá. I already compiled a list of some on YouTube. Kindly share any you know of cc @user @user @user @user | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user .@user nikon lo gba tear gas sara ni. Abi oponu le pe awon ara Ekiti ni? Ema fi pele pele paro. https://t.co/WbP5oERwf2 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àngéré ~ Ǹjẹ́ o mọ̀ pé ẹsẹ̀ onígi ni àngéré. Nítorí náà la ṣe ní Ẹ̀yọ̀ àngéré, èyí túnmọ̀ sí; Ẹ̀yọ̀ olẹ́sẹ̀ igi. #yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ṣé mùṣèmúṣè rẹ dá múṣémúṣé bí o bá gba ìbéèrè márùnún nínúu mẹ́rìndínlógún ìyẹn ni wípé mùṣèmúṣè rẹ dá múṣémúṣé ó yá dáhùn ìbéèrè | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo fẹ́ràn rẹ̀ kọjá bí mo ti lérò pé n ó fẹ́ràn rẹ̀ lọ.. . Ní pàápàájùlọ (pé kò jo ti àgbékalẹ̀ ìdérùbani Nollywood) ti Ìran ìbálòpò.. . Síbẹ̀síbẹ̀, àwọn àgbọn kan wà nínú ìwé náà tí ó wù mí kí ó jẹyọ nínú eré náà – nípàápàjùlọ apá èyí tí ó dá ló... | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ifá sọ ìtàn nípa Ògún àti Òṣóòsì. Ọdẹ làwọn méjèèjì ń ṣe, tẹ̀gbọ́n tàbúrò sì ni wọ́n jẹ́. #Yoruba #Isese | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""Ẹni tó yá ẹgbàafà tí kò san án, ó begi dínà egbèje"""""""". Translation: """"""""He who borrows 1200 and does not pay back, blocks th… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ahhhhhh! Oloseluuuuuu! Ki lo wa de? Ede wa so Dokita Jonathan di obo. @user @user eri nkan bayi http://t.co/1oc3JHxPDZ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""""""""""@user @user @user : Awon omo Naijerians lo fa idi ti oro abo se mehe... http://t.co/3ztLDKWMBd"""""""""""""""" | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Baba mi a máa wí pé """"""""Apẹ́jẹ kìí jẹ̀'bàjẹ́"""""""". Hmm. #owe #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
hmm orisirisi yorùbátv ẹgbẹ ọmọ olúwa bí gbogbo àgbáyé ojú òpó ìkànsíraẹni yoruba tv | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ayé ò ní pa kádàráa ẹ dà. Kádàráa tèmi tìrẹ ò ní burú. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bóo wá ni a ṣe ń dá irun ará inú aàfin mọ̀? A ó sọ̀ yẹ lọ́la ẹ ẹ ọjọ́ ire. Ire o! #AwaLaNiIrun #Yorùbá | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Lionheart o ki n se eré tí ó dára nìkan sùgbọ́n tó tún fa Nollywood kúrò nínu pàlàpálá tí ó wa. ìbẹ̀rẹ̀ ohun titun láti ibití àwon ẹgbẹ́ẹ eléré àti àwon òsèré ọ̀dọ́ tó sẹ n dàgbà mọ̀ wípé ó seése láti fi Naijiria sórí máàpù eré tí àgbáyé | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ìjìnlẹ̀ Fíìmù. . Fíìmù tó yani lénu tí o máa gbádùn. . Eléré tó dára ni Damson, ó gbé iṣẹ́ rè dáadáa….Kúusé Ade.110% | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé Revd. Henry Townsend l'èèbó àkọ́kọ́ táwọn aráa Abẹ́òkúta yóò kọ́kọ́ f'ojú gánánní? Ọdún-un 1843 l'ọ̀gb… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ṣàǹgó olúkòso iná lójú iná lẹ́nu get some ancestral highness with this short oríkì of ṣàǹgó ọmọ ẹwélérè ẹ bu omi ìwúrí àwọn alálẹ̀ díẹ̀ lura pẹ̀lú ṣókí oríkì ṣàǹgó ọmọ ẹwélérè yìí by àṣàbíọ̀jẹ̀ afẹ́nápa | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user O da ti ofin ijoba Nigeria ba gba yin laye lati se. Itiju nla lo je fun wa lehin adota odun ominira pe ... | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ jọ̀wọ́ ní ìgbà wo la máa rí i wò ní uk | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user eku ogbon,anreti itan na | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ti biafura ba fe lo eje ki won malo ko si eni ti oma juwe ile igbe fun agbepo omo karo ojire e je ki a so igba wa efi oro yanmiri sile | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Ojumo ire ooo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àbùkù nlá gbáà lójẹ́ pé kòsí irúfẹ́ ẹ̀rọ iṣẹ́abẹ tí wọ́n nílò ní adúrú naija | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
aaya do mi mi mo omo ti e fun lomu omolomo laa ran nise de torutoru | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
awon yahooyahoo yi shahahahahaha ah ọ̀gbẹ́ni tẹju má pa mí o | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bámúbámú ni mo yó, mi ò mọ̀ pé ebi ńpa ọmọ ẹnìkánànkan | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ÒWE YORÙBÁ (YORÙBÁ PROVERB) Kókó Inú Òwe: Ìtọ́ka sí ìṣe ẹwà ilẹ̀ẹ Adúláwọ̀. Proverb Theme: A reference to African fashion flair. Ẹ lè wo fídíò rẹ̀ níbí👇 (You can watch the video here👇) https://t.co/ETDQFo7jRO #yoruba #yorubaproverb https://t.co/vb4kcWbv4Z | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fíìmù tí o dára. . . . Mo ṣìyèméjì bóyá kí n wò fíìmù náà kí n to ka iwe rẹ̀, ṣugbọn lẹ́hìn ìgbà tí mo wò fíìmù náà,ara mi ya gágá nípa ìwé àti ìtàn rẹ. Fíìmù tí o dára ni,má ṣìyèméjì nípa rẹẹ | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
A óò ké pe Olódùmarè, a ó bá a wí ire, fọ ire, sọ ire kí ti wá ba a lè dára. #AsaIwure | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ajíire o. Ají bá àìkú baálẹ̀ ọrọ̀. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ǹjẹ́ o mọ̀ pé aku ni ń pe àwọn yorùbá látàríi ẹ kú a kú tí a má ń sọ bí a bá rí iraa wa ie a kú ọ̀rọ̀ ìlú wa yìí o | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àfọwọ́fà ni àwọn ìṣòro tí ń kojúu wa lórílẹ̀ ayé tí àwọn ẹ̀dá mìíràn ń ba wa gbé yìí ọmọ ènìyàn ti kí ojú bọ ìbọ̀kubọ̀ a ti tẹsẹ̀ bọ pòòlò ìdágbẹ́ ti gún wa lẹ́sẹ̀ a wá ń ta lákáláká tombó tọ alábẹ lọ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fíìmù to kò dára tí kò sì mú ọgbọ́n wa | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ni mo fi ń kọrin lójúmọ́ wípé kí a ṣọ́ra fún àwòkọ́ṣe tí ò ní láárí, tí ò níbì kan tí yóò gbé wa rè. @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
inu awon kan kodun si aare buhari lori bio tise pase fun awon ologun ki olosi gambia | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
òwe àgbá ní kuduru ni ẹmi ń so ara ẹmi la ti yọ òrí tí ń ṣe ọmọ aráyé lóore | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Latii ma ko oro ni yoruba ko rorun o #tweetinyoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
bí agbada ò bá gbóná àgbàdo ò leè ta if the frying pan is not heated up the corns cannot pop good things do not | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#OrisunEasterGiveaway #30DaysGiveAway #Day8 TANI ALEJO WA PE NI AWOKOSE WON NI ORI ETO OJUMO IRE NI OJO AJE TO KOJA #Yoruba #Nigerian https://t.co/AJxPF7fAev | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ máa pé kó ṣẹ! Owó á wá wa wálé..."""" 🎵 #iwure #OjoAje #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fére ~► asthma. Fèrè ~► flute, whistle. Fère ~► to sip. Fẹ̀rẹ̀ ~► early morning. #InYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nípa eré to gbajúmọ̀ yí #KOB nko lè sọ pé ó dára tàbí burú ju àwọn ìyókù nollyhood lọ | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: “@user: @user Ase waa, koribe kosebe! To ri sese sese ni ti ilakose. Mo danu duro naa... @user #EndTer… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ta lòpè, ta lọ̀ta ń'nú ikọ̀ @user àti @user? Ta ni yóò jáwé olú borí? #IdanOriPapa @user #tweetYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user. Akii dupe ara eni se ilu taa tedo sori oke le farasin ni? | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
1825; Aláàfin Májòótú fi ọmọ rẹ̀ fún Hugh Clapperton àmọ́ ìyẹn kọ̀ ọ́ #tweetYoruba #OyoIle #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
wọ́n ti da ọpọlọ wa rú dúdú ò dára ti wọ́n sọ ló fa arabíbó | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìgbélárugẹ ti wa n ti wa lá á mú ìdàgbàsókè bá ìlúu Nàìjíríà. Kàn sí @user fún bàtà tí a ṣe ní #9ja | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Irọ́ lẹ pa, goan open jàre 🤨 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ṣẹ̀ṣẹ̀ l'ọmọdé ńyọ̀ mẹ́yẹ, oṣó àtàjẹ́ ayé, ẹ yọ̀ mọ́ mi. Gẹ̀gẹ̀ ni à ń gbé ọmọ tuntun. Kọ́mọ aráyé ó máa gbé mi gẹ̀gẹ̀ lọ́dún tuntun.#Iwure | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ẹní bá fẹ́ jẹ iṣẹ́ ẹ̀ pẹ́, máa ńbínú mọ níwọ̀n ni. Whoever wants to long enjoy the fruits of his labor ought to be in… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user hahaha. Kòfẹ́sọ̀ kẹ̀? Òkè wo ló gùn tí kò fẹ́ sọ̀? :) | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eniyan o ton ra re bi Iya beji.... ejo, ewo ninu yin ni tan Aaare @user https://t.co/EUVwduTyeO | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Inú mi dùn nígbà tí ọ̀dọ́mọdé kan ládùúgbò fi ara tuntun tí ó fi aró dá sára aṣọ hàn mí. #YeMaaSun #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ̀ẹ̀mẹ́ta là á pajé ajé ajé ajé gbére tèmi kò mí ajé olókùn yóò bá wa rẹ́ láṣẹ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọ̀gbómọ̀ṣọ́ tóyèjẹ kọ̀ ìwọ̀sí tí oníkòyí fẹ́ fi lọ àwọn ọba yìí àìfinipeni àìfèyànpèyàn ló ń mú ará oko sán bàǹtẹ́ wọ̀lú èyí ló mú oníkòyí mú ẹdun gbógun tí ó fi ṣe kakanfò òmíràn láti ma tako kakanfò tóyèjẹ ní ìlú tó ní olú aláṣẹ àmọ́ kakanfò | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
awa ni ye oooose o n lo dada | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀kàndínlógún tó lóun ò bá oókan ṣe, à ti di ogun rẹ̀ á nira / The number 19 that refused to be added to 1 will find it tough to become 20. [Build bridges and foster collaboration; we need one another: together each achieves more.] #Yoruba #proverb | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Bàtà orí àkìtàn náà re òde ìyàwó rí. / Those pair of shoes on the refuse dump was once worn to a wedding. [Change is i… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user E ku ojumo. A kin bokurun eye lori ite. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""@user: Dárúkọ orúkọ mẹ́ta tí ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú 'Lá'. #Ibeere #Yoruba""""""""Labake, lashoore, Lanloye | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ògún máà mà jẹ́ kí n rí ṣonṣo. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Akin Ọ̀tún, Akin Òsì, Aláàfin Ìpekun. #Oranmiyan | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: @user @user Ehn ehn, Rev. J J Ransom Kuti ni."""" Bàbá bàbá Olúfẹlá ni #JJ, bàbá Fẹlá nìyí, #Isreal Olúdọ̀tun. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
èèwọ̀ sì ni ní bini kí ọba ó fi orí ìtẹ́ rẹ̀ sílẹ̀ fún ọjọ́ kan èèbó ba àṣà jẹ́ wọ́n da orí ìṣe kodò | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹni tí Ọlọ́run bá sẹ́'gi ọlà fún, kó ran ọmọlàkejì lọ́wọ́ #TweetinYoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ta ló bí ọmọba tó di ọọ̀ni ní ifẹ̀ ta ni ọba tó kọ́kọ́ jẹ ní ìbíní ta ni ogiso ogiso wo ló jẹ kẹ́hìn | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nigeria Television Authority (NTA) Ìbàdàn, gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ṣe pẹ̀lú àwọn ilé iṣẹ́ ẹ̀rọ amóhùn máwòràán ní gbogbo agbègbè ní Nàìjíríà. Èyí tí ó fi ìdí múlẹ̀ ní oṣù Èbìbí ọdún 1977 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀nà sí kékeré dídára ti ṣẹ̀dá. pẹ̀lú èrò ọkàn tí ó dára ... | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Kò pẹ́, Àfọ̀njá àti Salihu ó gbọ́ra wọn yé mọ́, okùn ọ̀rẹ́ já, ó wá ku ẹni tí ó so ó. Làásìgbò bẹ́ sílẹ̀ ní Ìlọrin, Fúlàní pa Àfọ̀njá, wọ́n gba Ìlọrin, Ìlọrín sì bọ́ sábẹ́ àkóso Ṣókótó. #ItanFulani #Darandaran #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọrún kì í ṣe ọ̀run | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
oluwa yio funwase ni idibo ti o n bo yi e ma se je ka ja ibo ni ke di fun itesiwaju gbogbo omo nigeria | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Gbo gbo Nkan Owo olorun lowa #TweetinYoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
jije ati mimu topor yanturu | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.