text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
Ilú funfun báláú tí wọ́n tẹ̀dó sórí àpáta ńlá méjì, tí odò sì là kọjá. Ó ti wà fún ẹgbẹ̀rún mélòókan ọdún. #Ronda http://t.co/k73MXoee7J
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ lè máa kórira ará pé ọ pàdé ṣùgbón ọ kúrò bi ẹni pe ọ ọpọlọ rẹ kú.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
i really do wonder who has actually seen an egbére before ǹjẹ́ ẹyin ti ṣe alábápàdé egbére rí have y
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ǹjẹ́ ẹ ti gbọ́ wí pé ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó lábẹ́ àkóso @user ti sọ èdè Yorùbá di túláàsì nílé ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
alákọ̀wé o gbéra nlẹ̀ ọ dìdé orí rẹ sọre lónìí o ò ní kàbùkù àlọ ire àbọ̀ ire lọ́la olódùmarè
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìyáa Júníọ̀ àti ìyá mi jọ ń lọ'biṣẹ́ ni.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ipokipo ti eda ba wa laye adanwo ni ka loo re tori igba ti a o ba fipo sile
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọ kékeré jòjòló lọ̀rẹ́ Olódùmarè. #SaveMusibaudeen
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Ta l'o mo oluraja """"""""tile"""""""" ile ati ogiri, ti o fe maa raa lati orile ede China. Ile ise ti o nse TILE ni mo ...
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
1. Akọ àti abo. Abórí àti adárípọ́n. Ìwàlẹ̀ àti___ #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
yorùbá omo karo ojire omo odùduwà omo kaaro ojire oòdua a gbe wa o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí ìbọn tó gòkè, ọfà tí a ti ẹnu rẹ̀ bọ ewé-iná, idà jọ̀mọ́, àdá ògbó, ọkọ̀ àti kùmọ̀ ni à ń kó r’ojú ogun. #AareOnaKakanfo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
9. Òkè àti ilẹ̀, orí àti ẹsẹ̀, odó àti ọmọ odó,___ àti ọrún. #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ ǹlẹ́ o ẹ̀yin ènìyàn mi! Ẹ sì kú-u pọ̀pọ̀ṣìnṣìn ọdún tí ó wà lóde yìí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ irúu rẹ̀ la ó ṣe lókè eèpẹ̀ láṣẹ Baba wa lókè. Bí ọdún ṣe ń kásẹ̀ ńlẹ̀, a kò ní bá a lọ, a ó máa wà bí ẹ̀wá ṣe máa ń wà lọ́dọọdún. Èmi á báwọn ṣàmọ́dún.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn ìṣe náà fọ́jú pọ̀
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn yìí ṣá ó ga o tó bá ṣe ojúkorojú ni wọn ò bá ti kó ewé iyá fún mi jẹ torí ìbéèrè lásán
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
👉 Yorùbátv ẸGBẸ ỌMỌ OLÚWA BÍ GBOGBO ÀGBÁYÉ Ojú òpó ìkànsíraẹni 🇳🇬🇹🇬🇧🇯🇧🇷🇨🇴🇨🇺🇬🇭🇨🇮 Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba #yorubatv #yorubaweddings #ebi #asoebi #nigerianwedding #owambe #yoruba #oodua #oduduwa #ondo #oyo #lagos #kogi… https://t.co/GCRfkI1Qbt
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
The Island jẹ́ aláìní ìtumò àti aláìlérè.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Eré tó rọrùn to sì jẹ atinuda pẹlu ìgbéjáde tó lẹ́wà. . . Eré tó panilẹ́ẹ̀rín léréfèé tí ó sí kún fún ìtàkùròso tó mọ́gbọ́n dání tí ó sì tún panilẹ́ẹ̀rín. Nítòótó, eré náà kò ni lẹkọ, o sí je eré atinuda pẹlu ìgbéjáde to rẹwa.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ori mi ti n wu fun bi e tie se dami lohun daadaa yen e seun adupe ojumo rere ni yoo je fun koowa wa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user awon irumole o je ba wo je ebakeeba... #TweetinYoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nibo ni Dejo Tunfulu wa? https://t.co/IoT0EHyrdr https://t.co/mugCdv2FSA #TweetinYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
...tía máa ńkọ n'ílédìi wa. Báyìí la ṣe máa kọọ́. 🎼 Ẹ̀sìn Ògbóni dáa púpọ̀, fẹ́ni tó bá lonú kan. K'Ájíbọ́lá gbàdúrà wá bíi ti Labọ̀sìndé. Labọ̀sìndé awo òwúrọ̀, awo mímọ́ nígbà ìwáṣẹ̀. Ó fìpìlẹ̀ rere lélẹ̀ ẹ jẹ́ ká ṣe mímọ́' Ajíbọ́lá yẹn lẹni táà ń sìn.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
nítesíwájú ìwádìí fi hàn wípé ọsàn àgbálùmọ́ ní agbára láti wo àrùn ọkàn
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo ti di pèrègún etídò, tó bá dàmọ́dùn, mà á báwọn ṣàmọ́dún. Gúnnugún kì í kú ní rèwerèwe. Ẹsẹ̀ mẹ́ta ni ti àgbó."""" #Iwure #OdunTitun2018
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
À ti pé, k'áwakọ̀ ọkọ̀ ó baa kọ́ àṣàa à ń wa ọkọ̀ láì tẹ fèrè àìnídìí, kí a máa wa ọkọ̀ pẹ̀lú ìwà ìrẹ̀lẹ̀. #LagosHornFreeDay
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ kó owó wa padà. Hán! hán! kílódé, ẹ fẹ́ jẹ wá run ni. #OwooWaDa #WhereIsOurMoney
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ká máa sọ ọ́, ká máa kà á, kí a sì máa kọ ọ́ sílẹ̀ já geere. @user rọ obì àti ìjọba láti máa lo #EdeAbinibi kí ìrẹ́pọ̀ ba jọba. #IMLD https://t.co/1J3cRGzou7
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ta ló ní ìdáhùn sí ìbéèrè yìí ? Write the correct answer in the comment section ☺️ #languedoc #yorubaweddings #yoruba #englishlanguage #speak #sp #speaker #speakeasy #readytowear #realestate #readAwrite https://t.co/7ok8IDew8l
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user Ta ló mọ̀ o jàre. Àwọn ará Amẹ́ríkà wọ̀nyí, orí ẹlòmíì á kàn ṣàdédé dàrú ṣá.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ORI KARUNLELADOTA: IDADURO ATI ÌYÀSÓTÒ ÈTÓ WÒNYÍ (APANMO AWON ETO WONYI FUN IGBA RANPE) #Law2go #HumanRightsinNigeria #Section45 #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
tọ̀tún tòsì ni ẹyẹlé fi nkó ire wọlé
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ta ló sọ wí pé a kò ní ọ̀rọ̀ìperí fún rubber lédè a kúkú ní àwọn ènìyàn kò mọ̀ ọ́n ni yálà kí a pè é ní irẹ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré Nigeria Prince tayọ nínú ètò rẹ̀, èyí losi jẹ kí o jẹ àfikún sí àwọn eré ti o nííṣe pẹ̀lú ọ̀ràn
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: @user. E wo nise ni mo nla gun be eni ti won ribomi. Ko si ina. Jenareto gan o wulo mo. Ilu ti dojuru. Oba Ed ...
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
O Lord, let men know that You, whose name is Jehovah, are the Most High over all the earth - Psalm 83:18 ORIN DAFIDI 83:18 [18] Ki awọn enia ki o le mọ̀ pe iwọ, orukọ ẹni-kanṣoṣo ti ijẹ Jehofah, iwọ li Ọga-ogo lori aiye gbogbo. (#yoruba ) #Prayer https://t.co/Iq2G5XDj5c
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
beeni o ogo oluwa kiitan
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bí èèyàn pọnmi tà kó ṣá ti lówó lọ́wọ́ iṣẹ́ niṣẹ́ ń jẹ́ ẹ jẹ́ kí a tẹpá mọ́ṣẹ́
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kílọ́ńṣelẹ̀ kẹ̀ ẹ, ẹ̀yin tèmi. Ẹ kú afẹ́rẹ́ o :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
omo alaso noni aso omo asegi ta noni igi asiwere ni grand father owun le bu igi je cc
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
nkan mà wá dé o
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ṣé @user ni Fulani? Fulani @user ju ti Buhari lọ. Buhari ó. Lè sọ èdè Fulfude, Atiku gan-an ni ojúlówó Fulani - Segun Showumi Atiku, Agbenuso fún ìpolongo https://t.co/YTyCLmxFTC
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Owe ni eshin oro Oro ni eshin owe Ti oro ba sonu Owe la ma fi wa I can't forget my #Yoruba! My teacher was so good! https://t.co/ZbzdzOOpTX
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user Nílé nkọ́? àwọn òbí ò kọ́ wọn ni? Àbí fanakula náà tún ni nílé? :)
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn Òpìtàn ní Ọ̀yọ́-Ilé jẹ́ àwọn tí Aláàfin fi sùúrù àti ìfarabalẹ̀ ṣà, láti ní ìtàn ìlú lọ́wọ́. Ipò náà sì jẹ́ ipò àtìrandíran. Àwọn Òpìtàn náà ma ń mú ewì kíké, ìlú lílu àti lílu ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ fún Ọba mọ́ ìtàn pípa wọn.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
aare jonathan ti je gbese awon omo gambari ti fa ibinu yo ni kaduna awon eniyan ti won n gbe ni guusu kaduna
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ kúkú mọ̀ pé Oríṣiríṣi ìgbẹ́ ló wà. Bí ìgbẹ́ gbuuru, ìgbẹ́ ọ̀rín àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Bákan náà ni ìtọ́ pé oríṣi, ìtọ̀ àtọ̀gbẹ, ìtọ̀ ibà àti ìtọ̀ tó kù. Ilé ẹ̀gbín nílé ìgbẹ́, bí kò bá sì sí ilé ẹ̀gbin, níbo la ó ṣ'ègbọ̀nsẹ̀ sí? #AyajoOjoaileIgbeAgbaye
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
pe kini njẹ́ ẹ ti gbọpé ìkòkò ni baba ìṣásun bee sini aja lagba pepe
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ṣálángá = pit toilet (Ṣíji búu, ó ní """"""""ṣálángá lo ma kúsí"""""""" - Ṣíji abused him, he said """"""""you will die in pit toilet"""""""") #Learn #yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọmọ Yorùbá lèmi o! #finegirl #swagger #yoruba… https://t.co/07YxqzOXKQ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kò sí ọ̀rọ̀ tí a lè pè nírọ́ nínú ọ̀rọ̀ onígẹ̀gẹ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ati ogun ati oogun ati ogun nii n laa eni nii ogun dun nii ede
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré yìí jẹ́ ìyàlẹ́nu tí ó dùn gidigidi. Àwọn eré tó dálẹ́ ìtàn ìgbésí ayé ènìyàn má n dún gidigidi
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Ẹ jẹ́ ká dúpẹ́ lọ́wọ́ @user tí wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ #tweetYoruba --> http://t.co/52eEZngdRg
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user :)) Ẹṣeun ẹ kú àtìlẹ́hìn o :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
lọ́nà wo ni àti pé kí lẹ rí tí ó múu yín báhun
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ ṣé Baba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ará Ìbíní gbà pé #Osanobua ni ó bí #Obiemwen, Olókun àti #Ogiuwu. #Benin #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ọ̀rọ̀ ò dun ọmọ ẹṣin: a mú ìyá rẹ̀ so, ó ńjẹ oko kiri. / The foal really has no shame: it grazes about indifferently w…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Oju rere ati aanu, Alaafia to peye,Igbega lai si laalaa, Ki ẹ bi si ki ẹ rẹ si, Ki majẹmu Ọlọrun o sẹ fun yin,Isẹgun ọtaIbu…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Dájúdájú n kò f'ọwọ́rẹ̀ sọ̀yà. 'Detour' jẹ́ òmùgò gidi.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: @user ise ni oogun ise, ma f'owuro sere, oore mi.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ṣe ògbufọ̀ gbólóhùn yìí sí èdè yorùbá life is vanity
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bákannáà la ní kengbe (elépo), a ní àkàrà-ku (àkàrà tí a dín gbẹ, tí ó le). Àkàrà-lapata tí a f'àgbàdo pupa ṣe. #AlayeOro #Yoruba #Akara
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọdẹ gbójú bíi ẹkùn ̀bá
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ẹni tí yóò sọ irọ́ di òótọ́ yóò ja'gun ẹnu. / Whoever wishes to present lies as truths will have to war with his or h…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ewo ni tepe bami raja n raja se fa ija wa ti o ko ba ni oro gidi lati so e gbe enu yin l
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Alexis Sanchez ti so fún Arsenal wípé òun se àárè. Ó ye kí ó darapò mó àwon akegbé re ní ojó àìkú. #TweetinYoruba #TweetInYorubaDay https://t.co/kbxLJbmXT2
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: #EkitiDecides : A ti gúnlẹ̀ sí Ekiti láti máa mu gbogbo bí nǹkan ṣe ń lọ nínu ìdìbò sípò Gomina https://t.co/fHKZrG1qi8…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nigeria Television Authority (NTA) Ìbàdàn, gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ṣe pẹ̀lú àwọn ilé iṣẹ́ ẹ̀rọ amóhùn máwòràán ní gbogbo agbègbè ní Nàìjíríà. Èyí tí ó fi ìdí múlẹ̀ ní oṣù Èbìbí ọdún 1977
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo sá di Ọ́ o Olódùmarè. Ìwọ ni Ọba aláàbò. Ọba gbani-gbani. #Olorun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
emphasis on dialect in this tweet not just the general yorùbá name àtẹnumọ́ lórí ẹ̀ka èdè nínú kíkọ yìí kìí kàn ń ṣe orúkọ tí gbogbo yorùbá ń pè é
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: A) Ọjà Nígbàanì, tí ilẹ̀ẹ́ bá ṣú, àwọn ọlọ́mọge yóò múra, wọn yóò sì gba ọ̀nà ọjà lọ. Ọjà (lọ́sànán àti lálẹ́) ni wọ́n ti…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ ò ní kíló tún kan ọmọ yobá pẹ̀lú jẹjẹrẹ ọmú
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìlú mi tí ó l'óhun ti bọ́ lọ́wọ́ èèbó; alọ́ni-lọ́wọ́-gba-tọwọ́-ẹni. Ìlú mi tí ń sààmi àádọ́ta-ọdún-ó-lé-méje tí ó kúrò lóko ẹrú. #OmiInira57
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gboromi Di Eleru, ajinido Di Oko Eni #Yoruba.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bákan náà, ni ó túmọ̀ sí wípé àrugisẹ́gi tó bá ṣẹ́gi, orí ara rẹ̀ ni yó fi gbé e. #owe #yoruba #owoogede #yobamoodua
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
agba to lomi ninu kan kii pariwo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Support orile ede Yoruba #yoruba #nigeriahasfailedus https://t.co/fmZqgu87Vz
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eni ana ni Malamu El Rufai @user @user @user Itara lohun se wan"""" Agenuso Aare Jonathan. Dokita Ruben Abati lo so be ninu esi oro
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
lóòótọ́ bí a bá wo ìtàn yewájọbí tí a bá nínú ifá ó ní ṣe pẹ̀lú ìkúnlẹ̀ abiyamọ ó sì ní ṣe pẹ̀lú ọrọ̀ ọmọ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìtanijí gìrì ni èyí ọ̀gá ṣá ti lọ ó yẹ kí a já ara wa kí a padà sí ẹsẹ̀ àárọ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ká máà bá Òpó lọ ilé Olórò, ṣàṣà ni ohun ìjẹ tí ẹ̀dá ọmọ aráyé ń jẹ lóde òní tí ò ní èròjà àjèjì ń'nú, kí la ó wa ṣe? #AyajoOjoIle #Earthday
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ǹjẹ́ o mọ eré ìtàgé í ṣe dáadáa? Ǹjẹ́ ó hùn ọ́ láti kópa nínú eré oníṣe nípa ìtàn ogun Èkìtì Parapọ̀? Bí ó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, lọ fún ìjẹ́rìí sí dídára tó nínú eré ìtàgé ṣíṣe ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹta ní Mọ́kọ́lá, nílùú Ìbàdàn. #Ekiti #EkitiParapo #Ogedengbe https://t.co/YJECuWImSK
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó ń pẹ́ lẹ fi ṣe, ó ń pẹ́ tí ẹ̀rọ bá yọ owó mi bíi jìgá àbí? @user @user #poorcustomerservice #ibasepoalabaratomehe
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#TweetinYoruba oruko mi ni Kolawole Surajudeen, Abimi ni Agege ni ipinle eko, omo bibi ipinle osun ni awon obi mi. https://t.co/KGU9nNuywS
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ọ̀pọ̀ ló fẹ lápa láì lápá, béèyàn ò sì lápá, kò lè lápa. / Translation >>
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
️ = bọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá = bọ́ọ̀lù aláfọwọ́jùsápẹ̀rẹ̀ajádìí = ẹyin oríi kọnkéré =
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
E̩ DÁ ÀWỌN ỌMỌDÉBÌRIN WA PADÀ #BringBackOurGirls #Yoruba http://t.co/8ACCjpoyEt
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Daenerys abisiji lati Idile Targaryen, eni akoko lati Idile re,eni inaojo,Ayaoba Mereen,ati awon Andali,ati rhoynar #GOTyo…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àmọ́, àjọ àgbà ilé-èkọ́ ifácitì ti láwọn ò ní gbà ní tàwọn, àfi bí ìjọba bá gba tàwọn. Wọ́n ní ìyanṣẹ́ lódì ńtẹ̀síwájú #Education #Nigeria
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Olúwa ò!. . . . Kíni mo ṣẹ̀ṣẹ̀ wò fún bíi ọgbọ̀n ìṣẹ́jú yìí? Mo tiraka títí ṣùgbọ́n kò bójú mu náà ni! Báwo ni ẹnìkankan ṣe gbà á lérò pé ó yẹ kí wọ́n ṣe sinimá yìí jáde?
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ó dun láti wò pàá pàá tí ó bá ní òye èdè Igbo ṣùgbọ́n ní gbogbogbò,o jẹ fíìmù tí o dára
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
akú ọdún akú ìyèdun happy easter
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ko sijoba to tii gbiyanju losun bii ijoba aregbesola peter action
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
owó money owó hand òwò business ówo boil ówō he looked owò broom òwò a town in ondo state ó wó it fell
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
beni onirohin oju ogun ni rt ọ ti pẹ́ ti obìnrin yìí ti wà lẹ́nu iṣẹ́ ìròhin ojú ogun
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó ṣì lè jẹ́ igbá fínfín tí a ó ya àwòrán onírúurú sára igbá fún ọ̀ṣọ́ tàbí ohun èlò inú ilé. Ilé iṣẹ́ ńlá ni igbá fínfín. https://t.co/a1fS1ZGca6
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
♪♪ #Nigeria yìí ti gbogbo wa ni ... ♪♪ #SunnyAde #ANewNigeria @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mon lo nose mi ma rin losi ori oke to wa legbe ile mi ma wa pada wale wa sise
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train