text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
RT @user: Ọmọ Ọba ìlú ni Ajénifújà jẹ́ kí ogun tó kó ìlú wọn tí ó rán Baba rẹ lọ s'ọ̀run, tí ó sì sọ dí ẹrú kí ó tó gba ibẹ̀ dé oko…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹẹ̀ rí bí mo ti gbé omi mu gbùn-ún gbùn-ún. Ó tutù níní. Ẹ ṣeun. Odò tẹ́ẹ ti pọnmi náà ní gbẹ o!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
e ma so bee o aa di alakoba gidi fun yin bee na lemi se n kilo fun yinwaa ri to ba ya ejo lowo nin
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
nígbà yẹn wá ń kọ
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àṣẹ wàá baba ẹ kú àti
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
tiwa n tiwa làsà tiwa n tiwa lèdè tiwa n tiwa lòwe ọmọ ̀bá tiwa n tiwa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user A le pin ya rara. Ipinya ko ni isoro wa. Awa eniyan ni isoro ara wa.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìfẹ là kọjá òfin. Ìfẹ máa ǹ fi ọkàn àwọn èèyàn dára. #yoruba #yorubas #quotes #NigeriaDecides2019 #Nigeria #yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Fun iyera wo nipa arun korona ni orile ede Naijiria. #EdeYorubaDunLeti #yoruba #yorubanimi #photos ##photographylovers #photo @user City Gate, Abuja https://t.co/Fa7tS7JZzG
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
... Má fi ire pe ibi, má fi ibi pe ire, má mù ú òmúlùmú, má fi òlòlò fọ́bùn. 📝 #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Eje ki abere lowo awon jegudu jera adari wa oooo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
dárúkọ irú ìlẹ̀kẹ̀ mẹ́ta
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Háà! Ó ga o!
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Èyí ni nọ́mbà ìwé ìrìǹnà àwọn èèyàn ọgọrùn tó l'òfin àyẹ̀wò àrun #COVID19 lẹ́yìn ọjọ́ méje tí wọ́n wọ orílẹ̀-èdè Nàìjírí…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nàìjíríà yìí ti gbogbo wa ni, ko máa gbọ́dọ bàjẹ́, ẹ jẹ ká so'wọ́ pọ̀ ká fi ìmọ̀ s'ọ̀kan, gbé e k'émi gbe"""" #Orin #KSA #Yoruba # Nigeria
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kò ṣe é wo.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Lékèélékèé ò yé ẹyin dúdú, funfun ni wọ́n ń yé ẹyin-in wọn. Ire ni tèmi, ire mẹ́tẹ̀ẹ̀ta. Aburú kan ò ní mi í ṣe, funfun ni ẹyẹ ń ṣu. Ire ni ọ̀rọ̀ mi máa já sí. Àṣẹ wò ó! Àṣẹ wà á! Àṣẹ wà á wò ó!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Amin edumare """"""""@user: @user odun de,odun olowo,odun olomo, Edumare je ki asopo re oo.*singing in yoruba*
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
A kú àyájọ́ t'ònìí o, àwa èwe gbogbo #OjoEwe
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mi o mọmọ sa fun ile ẹjọwon fẹ pami ni mo fi sa nilu nnamdi kanu
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ló jẹ́ n fẹ́ sọ nípa oyin, àti bí a ṣe lè dá a mọ̀. #oyinigan
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ounje ajeju ama muni sanra. E je ka jeun n'iwon. #TweetYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹnikẹ́ni tí ó bá jókòó láti wo fíìmù tí kò lórí ti ko nídìí yìí kan mò̩ó̩mò̩ fi ara rẹ sílẹ̀ fún àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ abaniló̩kànjé̩ ni
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Mo sá di ọ́ o oba alágbára ńlá.Tèmi dọwọ́ rẹ o Olódùmarè.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user 😃😃😃 Bùọ̀dá Dékọ́lá, ẹ kú àti!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
simply wonderful how the has turned positively around by the advent of àfi ẹni tí yóò bá pẹ̀gàn àjànàkú lá lóun rí nǹkan fìrí báa bá rí erin ká wí give credit where credit is due on course
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
B'áàwẹ́ bá i le parí, ẹni tí ò gbààwẹ̀ r'ógo, kí la ó gbọ̀ ọ́, wọ́n á sọ pé """"""""ojú ti ajọ̀sán"""""""". #AlayeOro #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ káàárọ̀ o. Oòduà á gbè wa o. Lónìí ọ̀jọ̀ bọ̀, ní ti Wíbẹ̀ Jẹ́bẹ̀ ohun gbogbo tó ti rẹ̀hìn láyé wa á bọ̀ padà sípò. Àṣẹ @user
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gẹ́gẹ́ bí Fẹlá ṣe sọ, """"""""""""""""ó ní ohun tí a wá ṣe ní yàrá, jẹ́ k'á bẹ̀rẹ̀!"""""""""""""""" #Toro #Sisi #Owo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: agbebo adiye to mu adiye iranna lo, e ran leti o pe adiye iranna ki se oun a Je gbe o.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Álúfábẹ̀tì tí ó wà nínú Álúfábẹ̀tì èdè òmíràn, ṣùgbọ́n tí kò sí ní ti Yorùbá, a ma pàrọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú Álúfábẹ̀tì Yorùbá tí ó sún mọ ni ohun. B/A: CH-ur-CH - Ṣ-ọ́ọ̀-Ṣ-ì Uni-V-ersity - Yuni-F-ásitì V-ideo - F-ídíò PH-one - F-óònù CH-rist - K-írísítì
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìràwọ̀ tó tan iná tó mọ́lẹ̀ jù tí ó sì sún mọ́ òṣùpá ní òfurufú ní alẹ́ àti ní kùtùkùtù òwúrọ̀ ni à ń pè ní ajá òṣùpá
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: #OroRanpe : Ọmọ ilẹ̀ ni wọ́n, tí... |#EdeYorubaDunLeti #Yoruba #workingfromhome #Nigeria #WednesdayMotivation #poem #si…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Ajinde ke? Jesu nikan ni Ajinde ninu oku o!
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Tí èfúùfù ọ̀gìnnìtìn yó máa fẹ́ yìì, yàà, á máa fẹ́ yòò, oòrùn gbígbóná yẹn náà a máa jó 'ni lára fòfòfò ní kíjankíjan. #Layeoye
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user 🤣 🤣 🤣 🤣 🤣 Set àwọn èkúté got me ROTFL Mo kúkú ti yí padà, I've been fighting the urge to """"""""""""""""eat"""""""""""""""" something since. I've been taking water instead, mi ò kí ń ṣe set àwọn èkúté 💪
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìtàn ńlá nìyí.. . Sinimá tó yáyì gidi ni. Ó sọ nípa ìbàjẹ́ àwùjọ wá. Ó bani lọ́kàn jẹ́ ṣùgbọ́n òótọ́ ni.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ó sì gba àtùpà náà lọ́wọ́ wọn. Sugbon òrìṣà omi Ọ̀sun, sì sọ fún Tìmẹ́hìn wípé, wọ́n gbọ́dọ̀ ma jó bí àwọn àlùjọ̀nú náà tí ń jó yíká àtùpà náà. Ní ìwọ̀ oòrùn, Ọba ma jó yíká àtùpà náà ní ìgbà méjì. Tí àwọn àgbà ìjòyè rẹ̀ sì ma tẹ̀le lẹ́hìn.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user :) Ó dá a o. Ẹyín náà lè ṣeré lọ sí > http://t.co/4R7YMduGAS <
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
iran ti o mo olorun won gege bi iran ti o mo olorun won bi a ba gba gbo ninu oro re awa y o se ife re
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Bótiẹ̀ jẹ́ pé wọ́n nparọ́ fún wa, ojú Ọlọ́run tó o. Agára Ọlọ́run sì tó wòó sàn, ó jù bẹ́ẹ̀ lọ!!
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀kànràn kan yìí náà, iré dé. Ewé àjẹ́òfòlé ni yóò fo Ibi nù fún wa. #Iwure #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí a yéé bu-ẹnu-àtẹ́-lu ayárabíàṣá, pé òhun ló ń fà á t'ọ́mọ'lé-ìwé ò fi kàwé mọ́ #IAFEE
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Ojumo Ire nii oo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ojúmọ́ to mọ mi lónìí, ojúmọ́ ire ni. Ire loju owó ń rí, ire ni gbogbo wa yóò má rí. Àṣe #Yoruba... https://t.co/reXNVGZjnr
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ìyá ni wúrà
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bí wọ́n bá láwọn ń lọ ẹ̀ jẹ́ wọ́n ò máa lọ ká mọra wa mo kú mọ̀ pé delta itsekiri urhobo ò ní tẹ̀lé wọn |
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ododo oro """"""""@user: @user àbí báwo?""""""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Erongba wa kii se lati si awon agbaagba lowo ise,sugbon ki awa na le ma ko ipa ribiribi ninu l'ilo oro ilu …
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Fun wa! """"""""@user: Elédùà, bàbá alágbára. Ẹni tí gbogbo ayé ń pe òkìkí orúkọ rẹ̀,olórí ayé àti ọ̀run, mo júbàà rẹ, jẹ́ ó se…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
16. Ṣàngó náà ni Olúkòso Yẹmoja náà ni Ìyá arúgbó Yàtọ̀ sí Ọ̀rúnmìlà, Ifá náà ni _____ #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ní ìlú Ìkòròdú, oṣù karùn-ún àti ìkẹfà ni a fi ń ṣe orò. Orò ọdún Màgbó ni a ṣe lánàá. Líwẹ̀ di oṣù tí ńbọ̀. #AsaOro #Yoruba #Ijebulahun
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ninu akoko lent ti a bẹrẹ leni gbogbo ẹni ti oba jí owó wa nílu yi irandiran wọn má ṣofo danu gbogbo alọni lọwọ gba n
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Orí igi tó wọ́ làá wà, tí àá ti rí èyí tó tọ́. / It's while on a crooked tree that one will discover the proper one. [Don't despise wherever you are; it may well be a stepping stone to greater heights.] #Yoruba #proverb
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
e fun wa nina
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ilà àwọn èèyàn tó fẹ́ wọ mọ́tọ̀. Súnkẹrẹ ọjọ́ Àswàní yàtọ̀ #Tuesday #Aswani #Traffic @user #745am #Jakande http://t.co/2mvYSSc5U2
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí a bá dé ìlú táà léèyàn, ìwà rere làá ní. / If one is a complete stranger in a town, one ought to simply be of good character. [Good character pays: it attracts favour.] #Yoruba #proverb
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
èdè àyálò ni màámi mamamomma tí a fi mi kún ló di màámi bákan náà ìdọ̀tí ni dirty ti wa mílíìkì sì ni milk
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kò pẹ́, àwọn aráàdúgbò t'ó tọ̀ wọ́n wá sí igbó rí tẹ̀gbọ́ntàbúrò, ó d'ilé. #Iyewa
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òsì . . . . . Àwòrán ti kò ní kókó pẹ̀lú àwọn òṣèré tó lágbára pẹ̀lú ìwà àìní ìjìnlẹ̀
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Àwa yó ṣ'èyí tí orí rán wa. A ti pinu láti gbé èdè, àṣà àti ìṣe abínibí Yorùbá lárugẹ kárí ayé sáàbàdà! Májẹ̀mú ni. #OmoYorubaAtata ni mí.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Àṣẹ. Ẹṣeun ẹ wá jẹun.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Gbede nii ro koko lagbala...#ATUNTE @user: Mo kí baba àti yèyé ọmọ tuntun kú ewu ọmọ o. Ọlọ́run á wo ọmọ náà dàgb…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀dọ́ ní í di ọkọ, aya, olórí ilé, olórí ebí, olórí ìlú. Ipasẹ̀ ẹni t'ó ti jẹ́ ọ̀dọ́ rí nígbà kan sì lá á tọ́ ... #DGtrends
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Orúkọ tí a ma ń pe ọba Òsogbo ni, ÀTAỌJÀ ÌLÚ ÒSOGBO. The title of the king of Òsogbo is, ÀTAỌJÀ of Òsogbo (Ọ̀SUN STATE).
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user ... Ẹ̀ṣọ́ rógun ó yọ̀, ọmọ ẹyẹ ṣùṣù ẹ̀gà. #Oriki #Onikoyi #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
1. Àwọn ará ibí yìí mọhun tí wọ́n ń ṣe o, bí wọ́n fún-un yín ní kọ́bọ̀ kí wọ́n tó wọlé, Náírà ni wọn yó fi kó bí wọ́n débẹ̀ tán #Abameta
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
A ò ní gb'ojú orun d'ójú ikú. Ó di ojúmọ́, kí ẹ jí mi bí ẹ bá jí o. Àjípé o!!!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user epo ti tán láàárín ọ̀nà 🤣🤣🤣🤣 https://t.co/j4rCru1Mjf
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
oúnjẹ kì í ṣe ìṣòro ilẹ̀ yìí bí ẹ̀ta ṣe ń bẹ jaburata náà ni èso lọ lóríṣiríṣi lára àwọn èso ilẹ̀ẹ wa àgbálùmọ́ jẹ́kan
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ dá àwọn ọmọ wa padà o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
dájú-dájú owo ni kẹ̀kẹ́ ìhìnrere. #£$¥ :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀báńjìgì mo dúpẹ́ lọ́'ọ̀ rẹ fún oore jíjí ire
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀gbàgbà tí ígba'rá ilé tí ígba'rá oko. Olódùmarè ní íjẹ́ bẹ́ẹ̀!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
owó gegere tí ń gbà lọ́wọ́ akẹ́kọ̀ọ́ kíni wọ́n fi ń ṣe
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ará oko, ará Èkó ń padà sí Èkó. Ojú á tún 'ra rí o! #Ogun https://t.co/WLNXxEHMfd
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Oríi mi, dákun dábọ̀ tètè dá mi lóhùn kí ire tuntun ó bà mí. Ó bá tètè gbé aláwo ire kò mí kára ó tù mí dẹ̀dẹ̀ bí ọ̀gẹ̀dẹ̀. #Iwure
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Nnkan ti mo feran nipa awa omo Yoruba ni wipe, ija esin ko n sele larin wa, gbogbo esin lo ma n wa ninu idile kan soso. #…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àmọ́ mo ti tún dé bí ewé adé. Mo bọ̀ bí ẹ̀bọ̀yè. Mo lọ mo bọ̀ n kò b'ọmọ jẹ́.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó fẹ́ẹ̀ rí bí wọ́n ti ń ṣe àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ obìnrin ni Nàìjíríà àti ìwọ oòrùn Áfíríkà báşubàşu.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Nítorí wọ́n lọ bro orí ọ̀rọ̀ láti fi ṣe ìfihàn àwọn ẹ̀dá...
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Yàtọ̀ sí k'á fi irú sebẹ̀, kíni a tún ń lò, kí magí ó tó dé? #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Inú mi ò bá dùn kání mo gbọ́ Hausa. Mo fẹ́ran èdè yí. Ìyá mi gbọ́ Hausa tó jẹ́ pé wọn a máa rò pé ọmọ Kaduna ni wọ́n ni :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
gbogbo ọmọ tí wọ́n bá bí fún aláké tó ń jẹ lọ́wọ́ ní wọ́n ma kọ ìlà ọ̀yọ́ fún
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Obìrin sòwà nú, óni òhun òrílé oko gbe...*sigh* àsìrà ojà pómbélé! Shior cc @user @user
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọdún mo kọ́ lo agbọ́rọ̀káyé mo ma ń lòó fi jà fún ẹ̀tọ́ ọmọ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹni tí ó ti ta erèé rí, mọ irú irọ́ tí oníkengbé le pa. #EsinOro #Yoruba Àṣìtẹ̀ ni ẹní tí ó ta àkàrà rí.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bee ni o orin ayo lama ko loni ati ni igba gbogbo amin ase oba edumare
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nílẹ̀ Adúláwọ̀, oṣù Ọ̀wàrà jẹ́ oṣù irè oko tuntun, oṣù ìdáríjì; oṣù ìyẹ-ara-ẹni wò. #OIANUK = #BlackHistoryMonthUK #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
and things i know to be true gistas mi ọwọn for making my special day extra special mo dupẹ o a ṣe mọdọn
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Obìnrin tí a bá féràn kì í ní àléébU; Bee, Ìyàwó tí a bá féràn ni omo rè í wu ni.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
oko + òdú = ìkòròdú ò +gbé + orí +ẹlẹ́mọ̀ṣọ́ = ògbómọ̀ṣọ́ ì + jẹ + = ìjẹ̀sà
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kódà wọ́n yà ju wèrè lọ. @user ni Google so di Shadrach. Ẹ̀rọ atúmọ̀ wọn ti ṣáyó. https://t.co/nh23PH4Ceg
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user kí ló ṣe jẹ́ bẹ́ẹ̀? Bad agreement ti á jẹ́? Orúkọ ọjà àtijọ́ kan l'ó di """"""""Àgbádárìgì"""""""" kí a tó yíi sí Bàdágìrì. #Badagry
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Yàtọ́ sí wípé iyọ̀ ní agbára láti pa ìdọ̀tí; kòkòrò inú ẹran tán yányán. #Ebola
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nkan ti ń lọ. ----> #smwMotherTongue
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
saheed osupa yorùbátv ẹgbẹ ọmọ olúwa bí gbogbo àgbáyé ojú òpó ìkànsíraẹni □ yoruba tv
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo dupe l'owo Tanimola Anjorin ti o pese itan yi l'ori abisidiqu blog. #TweetinYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Okunrin Ti Aye Ti Ko Sile Ti Ri Aanu Gba Lowo Gomina Mimiko: Sebi awon Yoruba loni ori ti o gbeni ni i gbe ala... http://t.co/d…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Owe l'ẹṣin ọrọ, ọrọ l'ẹṣin owe. T'ọrọ ba sọnù, owe la o fi wa. #Yoruba #proverb @user How would you translate this? Have you got an equivalent in your native tongue? https://t.co/u3U7jUDvUy
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train