text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
láyé ijọ́hun abẹ́ ìṣàkóso ọ̀yọ́ ni gbogbo agbègbè ààlà ilẹ̀ yoòbá wà tí ìlú ọ̀yọ́ sì ń gba àsìngbà gẹ́gẹ́ bí oǹnilẹ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
fijilante yinbon pa adamu niluu kaiama ni ipinle kwara o ti dero ogba ewon alaroye
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
òwe wa tòní odò tí a bá fi ojú rénà a máa gbéni lọ our proverb for today the river that you take for granted can actual
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""""""""""@user: Mo ti ni Olorun ni olugbeja, ma sowo jere laye mi oo @user: ♫ Á dára, a kà ṣàì dáa ♫""""""""""""""""""""""""""""""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
1.Ahun 2.Yannibo 3.Irere. Kini iyato tabi ajosepo awon wonyi? #TweetInYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
15. #PariOweYii: Kàkà kílẹ̀ ó kú ilẹ̀ á ṣá... #ibeere #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
8• Ìsúnkì ọ̀rọ̀ tàbí ìpàrójẹ ni àkàà, yanrìn, àálẹ̀, balùwẹ̀. Fún wa ní àpẹẹrẹ mìíràn. #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
5. #Parioweyii Ọmọ tí a pọ̀n sẹ́yìn... #Owe #Yoruba #Ibeere
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Lẹ́yìn tí a ti kó ọ̀pá-m̀-bàtà jáde, àwọn awo yóò máa yí ‘de ní ṣísẹ̀-n-tẹ̀lé. #EyoOrisa #EyoFestival #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ògún dákun bá wa f'ẹ̀jẹ̀ wọn wẹ̀. Kí ọ̀bẹ ilé wọn ó kọjú ìjà sí wọn. Kí ṣíbí ilé wọn ó kọjú ìjà sí wọn. Kírin gbogbo t'ó bá wà ní sàkání wọn ó kọjú ìjà sí àwọn olórí orílẹ̀ èdè yìí tí ó bá l'ẹ́bọ lẹ́rù. Èdì, gbéra sọ kí o lọ di wọ́n. #EndSARS @user
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Há -► share {àkàrà ló há - it is (bean)cake that (s)he shared}• Há -► tight {yàrá yìí há - this room is tight}. #InYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Abule wo ni Lai Mohammed ti wa gan, sebi awon ara Ilorin gbon die, isokuso wo ni agbenuso ijoba Lai nso nipa oro aje https://t.co/GUR3Hx3jNT
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwòrán tí kò dára
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
d ó ga jù
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kòṣemawo ni fún àwọn ọdọ Nàìjíríà àti àwọn olólùfẹ́ sinima gidi. . Maa fojú sọ́nà fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ isẹ mìíràn láti owó Kunle Afolayan. Ẹ kú iṣẹ́.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ìtàn ìfẹ́ tí ó lẹ́wà. . . . Eré yii jó ni lọ́wọ́ bìi ẹ̀ya iná. Mo fẹ́ràn rẹ̀ lọ́pọ̀lopọ̀. N'kò sì lè dúró láti tun wò. Ìfẹ́ yii dára púpọ̀. Mo gbóríyìn fún eré ti orílẹ̀èdè Nàìjíríà
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ó ta ẹrẹ̀ sí Nollywood. . . . Eréoníṣe yìí pa ni lẹ́ẹ̀rín tí kò ní ohun ìwúrí tàbí ìwà ìmúdàgbàsókè kankan
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
♪ Pátá ń jábọ́ ọmọge lọ wọ ṣòkòtò ♪ - #AsoKobaleNiSoosi :(
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Awon eniyan jona ninu ijamba ina to waye ni Felele lonii https://t.co/VkVS2Gnxjn #TweetinYoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#iPhone mi ti rí ẹ̀wù wọ̀ báyìí o. Awọ yíyi pọ́npọ́n ni pẹ̀lú. :) http://t.co/9ZR8EEFE
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí o tẹ́tí kí o gbọ́, bó o bá fẹ́ gbọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì dáadáa, ìwọ lọ mọ èdè abínibíi rẹ dáadáa. #learn #yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn ọ̀rẹ́ méjì kan ń bẹ, ọba làwọn méjèèjì rèjì ń ṣe. Ó tó àsìkò fún wọn láti pa ààlà tí yóò dúró gẹ́gẹ́ bí atọ́ka ibi tí ilẹ̀ oníkálukú pẹ̀kun sí. Àwọn méjèèjì pinnu pé kí wọ́n o gbéra lọ́jọ́ kan, wípé ibi tí àwọn bá ti pàdé ara ni yóò jáàlàalẹ̀. #AalaPipa
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Clustered Colours' dà bí ìpanu tí kò wón tí kò sì ní ń kankan nínú.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kì í ṣe irú fíìmù tí mo fẹ́ràn, àwọn òṣèré tí mo fẹ́ràn ló ṣe é.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
we caught them young with ranging from ta ló wà nínú ọgbà náà to ẹyẹ mélòó tolongo wáyé believe me they didnt want anything more àwọn ọmọdé àti eré ṣíṣe
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí n f'ọwọ́ gbá 're mú, ọwọ́ọ̀ mi ọwọ́ ire, oríi mi orí ire. Ire ò lórúkọ méjì ire ni ire ń jẹ́. Ire lálẹ́ ire l'ówùúrọ̀, ire òwúrọ̀ kó bá mi kalẹ́. Ire gbogbo di oríì mi, ire Èdùmàrè! Ire àìkú Ire owó Ire ọmọ Ire ìgbéga Ire ìṣẹ́gun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Omode to BA ma se amodu eyin kise re lati ma mo... @user: RT @user: Ireti pipe ni fa irewesi okan. ... http ...
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ori yin o pe sir #2019in5words
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìmọ̀ tuntun ń jáde, bẹ́ẹ̀ ni ìmọ̀ titun nì ń fẹ́ kárí. À ń kọ ara wa nímọ̀. Ọmọ ọdún márùn ún ni a óò ti bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́. #Kiwontode
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
5. Kí ni ìtumọ̀ àkànlò èdè yìí : """"""""Fi ẹnu ṣáátá"""""""" Ọmọlọlá 'fẹnu ṣáátá' Adébọ́lá. #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kasala jẹ́ ìfowó, agbára àti àkókò ṣòfò tó ga jù. Ó kún fún àtúnwí, kò sì dùn.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
àwọn tó ń mú igbega bá àṣà àti ìṣe yoruba lọ́nà iwuri tunde kelani tí gbogbo ènìyàn mọ sí tk je osere tíátà ó máa ń ṣe fíìmù àgbéléwò ó jé olusotan ayàwòrán fíìmù àti olootu ere
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
*1897 ni, kì í ṣe 1873 ni dàárúdàpápọ̀ ọ̀hún wáyé. Ọdún tí aláṣìkọ, Àjàyí Crowther jẹ́ Ọlọ́run nípè. #Esuisnotsatan #SatanisnotEsu #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nlẹ́ o #london ìlú ìjẹkújẹ. ibi wọ́n gbé d'ànàmọ́ díndín pọ̀ mọ́ ìrẹsì jẹ.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#iroyin, #yoruba, Olakunle ma n lo sewon ree! Won fesun ole kan an, ni ko ba reni soniduro… https://t.co/Yti4yfYPiN
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user Àwa nìyẹn jàre. Àwa ò lè wá kú :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
nipa aabo ailewu ti awọn kokoro ti o le jẹun titi di bayi a ko ti ri boya spp tabi ati awọn kii kekere ti itumọ nipa google tumọ si laisi ẹri
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orí ni ère lọ́balọ́ba ńlẹ̀ifẹ̀ ìgbanì bí aláṣẹ èkejì òrìṣà bá yúnsẹ̀ òrìṣà dandan ni láti ya ère oríi rẹ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré ṣíṣe ti o yanilẹ́nu láti ọọ́wọ àwon òsèré àti àwòrán dídára tí ó da yàtọ̀. Mo wo eré yii orí mi si wú pẹ̀lu gbogbo òsèré tó ṣiṣẹ́ lóríi eré yii. Ìtàn naa si dùn àtí pé àwon òsèré ṣe iṣẹ́ tí ó dára lóríi eré naa.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ogbufo yi ku die kaato
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ajé ògúngúnnìsọ̀ kó wá bá mi gbélé mo fẹnu pe ìfà ìfà á wọlé tọ́ mi èjì ogbè á bá mi gbére wá àṣẹ wáà
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ikú àgbágbìí tún ti mú ọ̀kan lára àwọn àwòrò ṣàṣà eré ìtàgé ilẹ̀ Yorùbá lọ ọ̀run àrèmabọ̀. Bàbá Jímọ̀ Àlíù tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Àwòrò ti sáájú wọlẹ̀. Ó di gbére, ó d'àrìnnàkò, ó tún d'ojú àlá. #Yoruba https://t.co/XOZnS4nhUK
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ati pa asa ati ise wa re
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
èdùmàrè á báni dọ́mọ sí gbogbo òbí ni yóò jèrè àwọn ọmọ wọn ẹ kú ọdún èyin èwe
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Omo mo mo mo mo baba Oni Lu.. 5th and 4th #generational Drummer ... 🥁 “ ti pe ti pe “ Issa longtime thing . . . #yoruba #heritage #fatherandson #royalty @user Winnipeg, Manitoba https://t.co/fYEjGgCgBe
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọrọ̀, owó, Ajé ni ọ̀kan gbòógì ọ̀darànmọràn tí ó dá ìṣòro tí ó wà nílẹ̀ yìí sílẹ̀. Àwọn aṣebi, olubi àti aríjẹ nídìí mọ̀dàrú tí ó di ipò ilé ayé mú ò náání àlàáfíà ara àti ìgbé ayé tó lẹ́tikẹ fún ọmọ aráyé, ìfẹ́ ara wọn nìkan ni wọ́n mọ́. Ayé ń rí rúdurùdu.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ijoba apapo ngbero lati se eto isuna N7.9tn fun odun 2018. #tweetinyoruba https://t.co/rjTE21hSRL
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo féràn èdè abìnibìì mi. That's #YORUBA and I'm so proud to be one.... https://t.co/NdCfTiJxpL
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Orí igi tó wọ́, làá wà, táà rí èyí tó tọ́. / It's while on the crooked tree that one will find the proper one. [Do yo…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ahhhhhhhh! ewo aworan Zahra omo Ogagun @user ta ni ori iru omo ti o dun ti o lewa ti ko ni dibo fun baba re http://t.co/kJO89o4GzW
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
A ò jẹ́ orúkọ #Yoruba mọ́, bíkòṣe orúkọ Larubawa àti orúkọ èèbó, elòmìíràn kì í ṣe ẹrú àmọ́ ó fún ọmọ rẹ̀ lórukọ ẹrú. #Nigbatiwonlo #BHM
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìdáhún sí ìbéèrè wa àná rè é ó
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Fíìmù ti o ni àwọn gbajúmò Òṣeré nínú sugbọn ṣíṣe rẹ kò dára rárá
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ìjà ẹnìkan ṣoṣo kọ́ àjọ̀ṣe gbogbo òǹlò ẹ̀rọ ayélukára bí ajere ni ẹ dìbò kí ìgbìmọ̀ aṣòfin wa ó gbójú kí wọ́n lọ gbalé ságbójú ire o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bumping into one's role model is one of the best things that can happen to one's day. Inú mi dùn láti pàdé yín lónìí sir @user Òkè òkè lẹyẹ ń fọhùn, Continue to soar high! #GoogleforNigeria https://t.co/FBBwx7k3Js
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìjọba @user yóò ṣí ọ̀nà Kọ́láwọlé Ṣónibárẹ́ l'Ájàó lónìí. Lóòótọ́, iṣẹ́ àtúnṣe ọ̀nà yìí mú lílọ-bíbọ̀ ọkọ̀ rọrùn. Irú ẹ̀ la fẹ́. https://t.co/rQpGWVf3be
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ise ni o se da se owo o see da na
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
a kì í so ẹran mọ́ ẹran kí ìkan kan ìkan pa that two rams were tethered together is no reason for one to butt the
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
.@user eku ise takun takun. Enu opuro kin seje. @user ti ja iro yin. Fake news booming in Ekiti - six false reports around governorship poll - TheCable https://t.co/rS6eEZvvK7 via @user
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ara eleyi tun ya to oàrà ò ńtán nílé alárà
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èmi kì í ṣe onímẹ̀ẹ́lẹ́, ni mo ṣe mú iṣẹ́ àgbẹ̀ mọ́ iṣẹ́ oṣù. Àgbàdo, ewédú àti ẹ̀fọ́ ti ń gbéra ńlẹ̀. @user #NigeriansAreNotLazy #Yoruba https://t.co/24HB0BdjPu
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#Otoge ti le @user kuro ni ilu o Ki lo tun ku to yio se? Eni ti a belori ton senu wuye....🎼🎹🥁🥁🎷🎺🎸🎻 https://t.co/dEqPbLR6EB
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Àjànàkú kọjá mo rí nǹkan fìrí; bí a bá rí erin ká sọ pé a rí erin. #learnyoruba #Language #Yoruba #elephant #InYoruba http…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àwọn alákọra àtọ̀hùnrìnwá onímúṣoṣoro yìí ti kó ọ̀pọ̀ ọmọ yorùbá lẹ́rú fúlàní ló ta àjàyí ìyá àti àbúròo rẹ̀ méjèèjì sóko ẹrú ní bí nǹkan
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ase edumare alákọ̀wé dúpẹ́ lọ́wọ́ elédùmare fún ìṣọ́ àti àbò rẹ̀ àjò ti ndópin wàyí o kí ọl
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Fíìmù tó dára gidigidi! Láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin ni ẹ̀rín àti ẹkún wà.Ó ṣe àfihàn ìfẹ́ Ọlọ́run àti agbára nínú nígbà ìkorò àti ìgbà ìkẹhìn. Òsùbà fún àwon òṣèré àti Olùgbéjáde fún Fíìmù tó le yí,ìróra,ìyà, ìfé àti ìṣégun níno Fíìmù náà.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ẹ wo bí ewé ti rọ̀ dàálẹ̀ bí òjò. --> http://t.co/M88ugxxf http://t.co/CAhM5yyP
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user ìyẹn ò ṣ'òro, kí a máa fi àdín àgbọn para, k'á yé é bóra. K'á di ṣùkú kí atẹ́gùn àlááfíà fẹ́ sí wa lórí. Àbbl! #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
nǹkankan ti oyìbó ṣe sí wa tí n ò fi gba ti wọn bẹ́ẹ̀ jùjù ni bí wọ́n ṣe fi ọgbọ́n àrékérekè gba tọwọ́ wa dànù
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó wà ní ọ̀kẹ́ ẹgbẹ̀rún 10 sí gúúsù Ọ̀gbómọ̀ṣọ́ Orísun ìmọ̀ yìí: Adegbite Folaranmi Adewuyi, Onipede Kayode Joseph, Igbon, Iresa, Ikoyi: A Prehistoric Relationship Till Present Time (in) 'Historical Research Letter, Vol 15, 2014
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#iroyin, #yoruba, Dereba to wa moto epo to paayan mokanla n'Ileefe lojosi ti foju bale ejo… https://t.co/EF91gQLGUd
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ere gidi.. . . . Eré tí Ìtàn rẹ lágbára nìyí. Ó yẹ láti wò. Mo rọ yín láti wò ó.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ànàá òde yìí ni Ọjọ́ Oúnjẹ Àgbáyé #foodday, ó ṣeni láàánú pé a ní ilẹ̀, onírúurú èso ọ̀gbìn, kí wá ló dé tí a ò lè fi ṣe oúnjẹ? #EndPoverty
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èkó Àkéte ò, Ọba jẹ́ ó rójú #Lagos
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Lóòótọ́, Nigeria #Koderun, ìṣojú ọmọdé kọ́ la ti ń ṣe nǹkan àgbá bíi ṣọ̀kí. Èyí ni ọ̀ràn náá fi ká 'ni níṣan. Ó ní irú ohun à ń ṣe lójú èwe.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user èèééoo! ẹ kú orí ire o! nígbà wo ni ìpàdé yín?
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo ń wá ohùn orin àti àgbéyẹ̀wò. . . . Ohùn orin kan wà ní ìparí Fíìmù náà. Ní abẹ́lẹ̀, kò ní ọ̀rọ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohùn aládùn ni ó jẹ́. Mo ń gbìyànjú láti wá orúkọ rẹ̀.. . . . Lẹ́yìn ìyẹn, Fíìmù ńlá ni, ó fi àpẹ̀lẹ́ púpò tẹ̀síwájú. Ìṣọwọ́ṣeré rẹ̀ bòjúmu. Kò sí ìmọ̀sílára tàbí ohunkóhun bíirẹ̀ tí kò bòjúmu. Àwọn...
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ẹ kú òwúrọ̀ o. Ojúmọ́ ire ni lónìí o. #ekaaaro
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Midnight Crew' jẹ́ eré kan tí kò dùn tí ènìyàn ni láti yẹra fún ní sinimá.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
eléyi....aaahh:) àwàdà leléyi
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Toò. Wọ́n ní ìlú kan tún ń bẹ lábẹ́lẹ̀, àti lábẹ́ odò yìí. Ìyẹn tún di ọ̀la ọjọ ire. Oùnjẹ ni ọpọ́n sún kàn wàyí. #Ronda #Andalucía #Spain
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ife alailegbe bi eyi ti edumare fi fe wa e ku ojumo oh
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
6. Ẹní, màá máa ní Èjì, ireè mi yóò dèjì, Ẹ̀ta, irúgbìn-ìn mi yó ta Ẹ̀rin, ẹkún-un mi yóò dẹ̀rín Àrún, mi ò ní kú, mi ò ní rùn Ẹ̀fà, n ò ní __ á tì #Ibeere #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ìgbin tó wá ẹ̀jẹ̀ lọ sí ilé alákàn, bó ti wọlé ni yóò padà jáde. / Any snail that goes to the crab's burrow in search…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìjà ẹnìkan ṣoṣo kọ́, àjọ̀ṣe gbogbo òǹlò ẹ̀rọ ayélukára bí ajere ni, ẹ dìbò kí Ìgbìmọ̀ Aṣòfin wa ó gbójú, kí wọ́n lọ gbalé s'Ágbójú. Ire o!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
[Cubaaz Yorùbá] Anfani nlanla wa fun awọn 300 ti o ba kọkọ darapọ mọ Cubaaz. Anfani wo ni yẹn o? E o ni anfani lati jere 20% bonus lori iyekiye ti ẹ ba nawo sori cubaaz. Jubẹlọ ẹ tu jere '100% bonus' lori iyekiye ti ẹ ba mu sile. #Cryptocurrency #Yoruba #Blockchain https://t.co/H5cfBfUxZh
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user B. Òkú ògolonto
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọlọ́ffà ni ó ma ń gbé igbá orókè láti lè fi ẹsẹ̀ àṣẹ rẹ̀ múlẹ̀ ní ìlú ọ̀ffà essa ma gbà wípé ohun fi ìdírẹmi nínú ìdíje náà nínu ọdún náà àwọn onílù ìbílẹ̀ olórin àti oníjó àwọn ọdẹ ma ṣeré lójú agbo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
alafia lawa eyin nko
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#burnaboyliveinconcert #burnalive was ........ Pls tell it in your own word!!!!💯💯💯💯💯 Like my #oduduwa #yoruba folks dey talk am """"""""Iroyin koto Afoju Ba"""""""" #issabanger #epic #masterpiece… https://t.co/8fMXEVecNl
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
aláwàdàa nì fúnwọntán ṣe rẹ́cọ́ọ̀du oríṣìíríṣìí bíi àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
À gbọdọ̀ wò ni.. . Fíìmù ère ìfẹ́ tó fani mọ́ra ni. Mo kàn pinu láti wò ó wò ní nígbà tí mo rí I lórí Netflix, kò sì sí ohun kankan tí mo kó àbámọ̀ sí lórí rẹ̀. Àwọn orin tí wọ́n lò nínú rẹ̀ dára gidi ni.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Níparí eré orílèdè Nigeria tó lágbára, fún òpọ̀lopọ̀ mò ún nírètí pé orílèdè Ngeria ma pèsè eré tó lágbára, àti ibè ni àwon arákùnrin Esiri tí má wolé
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ohun àbùkù ni fún ọ̀dọ́mọdé, láti na ọwọ́ sí àgbàlagbà, fún ìkíni. Èyí tí ó tako ìlànà ìtẹríba tàbí ìdọ̀bálẹ̀/ìkúnlẹ̀, ní ilẹ̀ Yorùbá
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ogun ayé ò ni ìgbà ìsimi, ogun ayé ò ni ibòji, o d’ijọ́ a bá dé ‘bojì. #OgunLaye #YorubaPoem #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ogun ìran fúlàní darandaran dáràndáràn ni ìkíni àwọn ará ibí yìí ti ń gungi kọjá ewé wọ́n ń mú ayé nira fún ìran yorùbá pàápàá nàìjíríà
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọ̀túnba gani adams ni karùnúndínlógún wo àwòrán àkójọpọ̀ orúkọ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwòrán yìí fi hàn ibi tí epo ilẹ̀ yìí ti ń wá #BBC ~> #NationalConference #ConfabNG http://t.co/j8NnB6v1DI
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọ̀kan nínú àwọn igun odi lọndọn ayéàtijọ́ ni o
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọwọ́ ẹ̀gbin ni ọwọ́ òsì jẹ́ òun ni a máa sábà fi ṣẹ̀gbin nùdìí lẹ́yìn ìgbọ̀nsẹ̀ àbbl ọwọ́ òsì náà ni ọwọ́ àlàáfíà
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train