text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
kí olódùmarè rí sí ìlọsíwájú àti ìdàgbàsókè ìlú wa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
mo ti n tele bayii omo ipinle oyo ni mi mo si nife si ohun daadaa ti e dawo le yii | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
o morúkọ igi àṣórí ní gẹ̀ẹ́sì bí ẹ̀bùn owó ìpè igba náírà wá fún ọ bí o bá mọ̀ ọ́n | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
yoba moodua fi èdè yorùbá kọ́ ọmọ rẹ̀ teach your child yorùbá | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
beeni itan fi ye wa wipe arabinrin flora shaw to je iyawo tabi orebinrin lord lugard ni o so oruko yii ori | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Awimayehun, Alagbada ina Alese lewi, Alewi lese, Adagba maparo oye, Alawotele orun, Alade alafia, Alade ogo, Alade nla, ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èyí mú omi inú tòun tòde kan ìjàpá, ó ní òun náà yí ò lọ dáko kòkó, kí owó ba lè pọ̀ jantirere lọ́wọ́ òun bíi ti ajá. #Itanilumasee | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Oríi mi rè é, orí ire Ọwọ́ọ mi rè é, ọwọ́ ire Ire kò yaléè mi kíákíá Nítorí kíákíá ni mọ́tò ń rìn Kíákíá ni kìnnìún-ún lẹ́ranbá Kíákíá ni gbogbo àdáwọ́léè mi yóò yọrí sí rere láṣẹ Elédùmarè. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àkàlàmàgbò kì í rọ̀run ń màjèsí, àyàfi tó bá darúgbó. Mà á gbó, mà á tọ́, pẹ́ láyé bí mọpẹ́ ti í pẹ́ láṣẹ Èdùmàrè. #Iwure #OdunTitun2018 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: @user ekú àmojúbà odún òròmíyan ní ìlu ifè Ninu osù ta wa Yí.""""Á kúkú báwa láyọ̀. Ọ̀rànmíyàn á gbè wá #oranmiyanfestival | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ni ọmọọba bá wí fún olùkọ́ àgbà ags wípé àbí ẹ fẹ́ ṣíwọ́ sókè lu ọba ni | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Eniyan laso ooobo ni ni ara ju asolo • """"""""@user: Ẹbí, ará àti ọ̀rẹ́ ṣẹ pàtàkì jú owó àti ọlá lọ."""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èròjà a dín ìlera ara ẹni kù ni dioxin t'ó jẹ́ gbòógì nínú ike tàbí ọ̀rá. #IjambaOraAtiIke #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
tàbí kátọ̀ọ́lé tọ̀ sínú ààrọ̀ ẹ̀ṣẹná á sì ma rà á lábẹ́ èyí ni tọ̀ọ́léọ̀ọ́lé á rántí lójú orun | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Wọ́n ní káa máa lo èdè abínibí wa lójoojúmọ́. Ká máa sọ ọ́ sírawa láwùjọ--> #smwMotherTongue cc @user @user ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
“@user: Olorun anu; SA nu fun mi. http://t.co/CbjlARGxud” àti èmi náà o Olúwa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user @user @user Àwọn tí Èkó náà kọ ọ̀rọ̀ ránṣẹ́, wọ́n ní kí n wá kí á fi ojú rinjú, kí n sì gbé agolo ọtí @user ọ̀hún dání fún ìṣèjẹ́rìí. #EtoOnibaara #consumerright #brandnegligence #LiveYourBestLife @user https://t.co/r91bBayWVm | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bírúu owó kan bíi I.T.F bá wà, nǹkan á ṣẹ́pẹ́rẹ́, àwọn ọ̀dọ́ tí ò ríṣẹ́ tó sì fẹ́ bẹ̀rẹ̀ okòwò á rí nǹkan jókòó tì"""" #OhunOdoNigeriaKan | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìbáṣepọ̀ t'ó ń bẹ láàárín Gẹ̀lẹ̀dẹ́ (ìyá ńlá) àti ilẹ̀ (Ògbóni) ò mọ níba, ilẹ̀ ni ìyá gbogbo ẹ̀dá, ìyá ni ilẹ̀. #Gelede #Yoruba #IWD | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Ki la gbe ki le n ju? | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Aì f'ọmọ Ọrẹ̀ í bọ ọrẹ̀, a ò ní bá ọdún 2015 lọ, ẹran àti ẹ̀jẹ̀ wa ò ní yí iyẹ̀pẹ̀. Ọ̀nà kì í dí mọ́ ọmọ ọlọ́nà, àlọbọ̀ ni ti wa.#Oduntuntun | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user. àpáará yín ga #AFCON13 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
O kọja bẹẹ, ẹ ó fẹ́ wọ fíìmù yìí, fíìmù náà jẹ́ oun tí e ma gbádùn yàtọ̀, Nollywood to dùn gaara | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user Kọ́ ọ nítorí àwọn ọmọ rẹ, kí wọ́n ba mọ̀ ọ́ @user #learn #yoruba so your kids can know it #speakyoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ire gbogbo a kàṣàì tọ̀ mí wá ire gbogbo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: 'Eni Eegun ba nle ko maa r'oju; Tori b'oti n re ara aiye ni n re ara orun' #Yoruba #Nigeria #AfricanProverb ..Translatio ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Otitọ ni. Kini ti a ba jẹ apakan ti ojutu kan nipa lilo #Yoruba ati awọn ede Afirika miiran nibi ni Twitter? Eyi le ṣe atilẹyin fun ijoba lati ṣe apakan rẹ. You check? #AfricanLanguagesDay #IsComingSoon cc @user @user @user @user @user https://t.co/pfOe1iQU9r | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
nínú oríkì orílẹ̀ wo ni a ti bá gbólóhùn yìí abẹnutónítóníọtíńmímu a ìran òjé b olókùn ẹṣin d onígbòórí | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ KÚ OJÚMỌ́ O... 😊 GBOGBO ÀWỌN ARÁ ILÉ Ń KỌ́? 🤷♀️ ÌGBÒKÈGBODÒ WA LỌ́SẸ̀ YÍ Ò NÍÍ JÁ SÍ ASÁN! 🙏 (Good morning... How are you and your household? Wishing you success in all your endeavours this week!) #yoruba #iwure… https://t.co/TLkUqprRra | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
KÙǸDI Ẹran tí wọ́n ti sá gbẹ fún ìgbà tó pẹ́, títí ó ma fi yi. Ó lè jẹ́ ní ẹran tàbí pọ̀nmọ́. Kí wọ́n tó sèé, wọ́n ma kọ́kọ́ rẹẹ́ sínú omi pẹ́, kí ó lè rọ̀. Ó pọ̀ rẹpẹtẹ ní àwọn ọjà àti ilé oúnjẹ ní Ìbàdàn https://t.co/F6ScdkEBcW | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mi ò le fọwọ́ rẹ̀ sọ̀yà | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ko si oro Yoruba fun """"""""Conjuctiva"""""""" naa la maa pe""""""""@user: What is the yoruba word for Conjunctiva? @user"""""""" | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Dídùn, dídùn l'ọsàn ńso. / Sweet, sweet fruits are what orange trees bear. [This year 2020 will bear nothing, but swee… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
A Yorùbá bàtá dance. Sit back, relax and, enjoy this beautiful Yorùbá art work. Ijó Bàtá Yorùbá. Ijó tí kò ṣe é f'ọwọ́ rọ́ s'ẹ́hìn, nínú àwùjọ ijó. Ẹ f'ẹ̀hìn tì, kí ẹ gbádùn rẹ̀. Source: Agogo Èèwọ̀ Movie https://t.co/RxLu2VwpTj | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bèlúbèlú ṣe yín rí? Àbí ẹ mọ ẹnìkan tí ó ti ṣe rí? Kí ni ẹ ti ṣe sí? Kí ni onítọ̀hún fi wo bèlúbèlú rẹ̀ sán. #Yoruba http://t.co/4tgkz7ghVL | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""@user @user Dokita to ju Senator Abe ti sope a o gbe Senator na lo ilu London Fun itoju to peye http://… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ibi ijóo ni a óò ti tú àṣìírí ìwà ìbájẹ́ gbogbo nílùú | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òkú náà àti ọmọ ta' jẹ́ aláìṣedéédé aláìbìkítà nínú ohun gbogbo. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ọba tó lọ́la tán tó ń yayé lẹ́nu, ẹ sọ fún un kó yéé símwín mọ́. Ikú kan náà tó pa Gómìnà ní í pa agbálẹ̀-ọjà. Ikú l'ọ̀gá gbogbo adáríhurun | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré yí kò kún tó. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user Ẹ máa wolẹ̀ o ọ̀rẹ́ wa. Ẹṣeun. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ ti ẹ̀ gbọ́ ná ọ̀gbẹ́ni yẹn ò rí ìlú lọ ni wọ́n ní ó gbé ààrùnkárùn wá | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré yìí kò tilẹ̀ mú orí ẹni wú rárá.. . Mo kàn fi wákàtí méjì àti ogún ìṣẹ́jú nínú ayé wo eré tí kò ní ọpọlọ àti láárí kankan ni.. . . . Kò dára rárá. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ohun t'ó bá jọ 'ra, ẹ jẹ́ k'á fi wé 'ra. Díẹ̀ ni ẹ̀sìn ìgbàlódé fi yàtọ̀. Ẹní bá ṣe àyẹ̀wò fínnífínní, yóò rí ìbámu. #Iseseday #Iseselagba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: NNPC don dry! Buhari is absent, Dino tí Sọ̀rọ̀ Sókè 🤷🤷🤷😂😂😂 Yoruba Nation Now! 📢📢📢📢📢📢📢📢 #StoneBadLeaders when you see t… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Rorò; meaning harsh, fierce {ilé ayé rorò - life is fierce} #InYoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹní tó mọ wúrà la ńtàá fún. / Gold ought to be sold to the one who values it. #Swissgolden #yoruba proverb | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ jẹ ń lọ sínú ìmọ̀ ìjìnlẹ #Yoruba #Nigeria #DemocracyDay #DemocracyDay2013 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èdùmàrè fún wa l'ómìnira tòótọ́ Gbà wá lọ́wọ́ òmìnira àfẹnuní Gbà wá lọ́wọ́ òmìnira orí-ahọ́n Gbé Nàìjíríà kúrò nínú omi ìnira... Ẹ kú ọdún òmìnira Nàìjá! #Ominira #nigerianindependence #Nigeriaat59 #nigeria #naija #yoruba https://t.co/pK7KfbHgtq | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ibò míràn tí a ti le kọ Yorùbá. (Another place that you can learn Yoruba.) https://t.co/t7vHNT69hh #yoruba #learnyoruba #duolingo #duolingo4yoruba #duolingoyoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bólú igbó bá jí, á fìbà fúngbó. Bí olú ọ̀dán bá jí, á júbà ọ̀dàn. Bí ayá bá jí, á júbà baálé. Bí ọmọdé bá jí, á júbà òbíi rẹ̀. Pírí ni mo jí sáyé, ́ ta ni ń bá júbà bí kò ṣe Adániwáyé, Ọlọ́run Ọba Olódùmarè. Ìbà Rẹ o! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àwọn nǹkan kan wà tí ó pọndandan tó yẹ ó wà fún ìgbé ayé ọmọ ènìyàn | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Oga ju! Jimoh Oloyin de...RT""""""""..@user: Ibú fàájì la wà. Òpin-ọ̀sẹ̀ la pè é. Àwa ò lè wá kú. #Igbadun #Kelele"""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ̀bùn Edùmarè ni ọmọ Ẹ̀rí ìfẹ́ rẹ̀ sí wa ni wọ́n Èdùmàrè à ń bẹ̀ ọ́ Bá wa wo àwọn èwe yè Fi wọ́n fún àwọn tí ń wojú rẹ fún ẹ̀bùn wọn Má ṣe jẹ́ kí wọ́n kú mọ́ àwọn òbí wọn lọ́wọ́ Èyí a wí yìí, kárọ̀ rọ̀ mọ́ ọn. #omo #ewe #ChildrensDay #Yorùbá #IYIL2019 https://t.co/1oxECxc5BH | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn sinimá nínú fíìmù náà jẹ́ ìpìlẹ̀ àti pé kò ní ìgbádùn púpọ̀. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user beeni o gbogbo wa la o fi owo pa ewu fi erigi jobi lase Edumare | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
12. Èwo nínú ṣòkòtò wọ̀nyí ni kì í gùn kọjá orúnkún - A) Jẹ́bà B) Kẹ̀ǹbẹ̀ D) Sányinmọ́tan #Ibeere #Yoruba #sokoto | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìran Yorùbá ní Ìpínlẹ̀ Kogi ni àwọn ará Ọkùn. Wọ́n tàn kiri ní Yagba-West, Yagba-East, Mapomuro, Kabba-Bunu, Ijimu àti ní àwọn àgbègbè Lokoja. Wọ́n ń sọ ẹ̀ka èdè bíi Ìyàgbà, Òwe, Ìjímù, Búnù àti owowo. Ṣùgbọ́n, Ọkùn ni ojúlówó èdè wọn. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
jẹ́ kí ńfìdí hẹẹ́ ni àlejò fi ńti onílé sóde let me just hang in here is how the guest takes over the house from t | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọjọ́ ọdún lọ̀rọ̀ ń dọ̀lẹ translation a lazy man gets serious on the dday | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fíìmù náà ti ṣe dáradára ṣùgbọ́n mi ò le mọ irú fíìmù tí ó fẹ́ láti jẹ́ àti kíni ìtàn náà títí di ìgbà tí mo dúró wíwó ibìkan ní àárín. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ọmọ jayé-jayé ni àwa ń ṣe o jàre. Ta ló m'ẹ̀hìn ọ̀la? | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ ṣeun o mo ti tẹ̀lé yín padà kíákíá haha ba wo ni mo gbadun ede mi gidigann m | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user ṣàngbà fọ́! Àjà ò fura àjà jìn! iná wá bọ́ sórí aṣọ gbáà. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ẹ ó jèrè iṣẹ́ o. Ẹ kò ní ṣiṣẹ́ dànù lásán. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ là ńtẹ ẹrẹ̀ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ là ńtẹ eruku muds and sands are stepped on differently varied situati | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
oro awon ara kano yii dabi oro aja ti a n tori e ja toni tani o n ja lehinkule ohun sebi ki aarun polio le kase n | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí ni tí wọ́n fi ń pa ọwọ́ yìí mà n tà wàràwàrà kẹ̀ẹ. *Sanitísà àbí kí lẹ̀ ń pè é? Ajé àwon ilé-iṣẹ́ kiní ọ̀hún ti bugbá jẹ wàláhì. #EBOLA | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọba o ṣé o. Àwọn kan ò jí mọ́, wọn ò mín mọ́. O ṣé e tèmi o #Ekaaaro | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọba saa oyèfùsì àti ọ̀túnba adéníran ògúnsànyà pẹ̀lú tos benson | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ẹkú ọjọ́ ìbí o! Àṣèyí ṣàmọ́dún. Àkàlàmàgbò kìí p'ọdún jẹ. Bẹ́ẹ̀ni iná táa dá fún igún, ẹyẹ míì la fi nsunjẹ. Ẹ̀ẹ́ dàgbà darúgbó o! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
tí wọ́n bá fi igbá òfìfo ráńṣẹ́ sí ọba ó túnmọ̀ sí wípé kí ọba náà gba ẹ̀mí ara rẹ̀ ìlú ò fẹ mọ́ lórí oyè wọn ò dẹ̀ fẹ́ ba ṣe mọ́ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
o wa lati ode orun | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
iṣẹ́ loògùn ìṣẹ́ bẹ́ẹ̀ náà iṣẹ́ loògùn òṣì ká má mọ̀nṣẹ́ ká má mòṣì láyé tí a wá o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àìfinǹkanpenǹkan ní ńba nǹkan jẹ́ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: Omo kekere o kin d'agba l'oju obi e #owe #Yorùbá @user"""" | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
pe kini rt njẹ́ ẹ ti gbọ pé a ti le ikú lọ ní ilé wá ati le àrun lọ o di gbére | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Afárá kìíní, ìkejì àti ìkẹta tí Erékùṣù Èkó ni ìdíwọ́ wà. Àwọn kan ní kẹ̀kẹ́ alùpùpù ọ̀kadà tí ìjọba f'òfin dè l'ó fa sábàbí 😶 https://t.co/TOglvtL6S7 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wọ́n fún ọ ní ọbẹ̀, ò ń ta omi sí i, o gbọ́n t'ẹ́ni t'ó sè é? #Owe #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
e le ran wa lowo ki a mo eyi toku | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àdúrà mi ni pé kí ọlọ́run ko ilẹ̀ wa yọ nínú ìpọ́njú kúrò nínú omi ìnira ẹ bámi ṣàmí àdúà | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ajé Olókùn. Ajé Onírè. Ajé Ṣálúgà. Gbé ire owó tútù tí ń d'óṣì-pa-àgbàànà kò mí. Bùn mí níre owó tabua, nítorí owó ló dùn ún jayé, láìsí owó, kò sí ènìyàn. #iwure #OjoAje #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó d'ọwọ́ ẹ̀yin ìyá o! Ẹ bọ́mọ yín ṣe o, kó rí bẹ́ẹ̀ o. #IWD2017 #Yoruba https://t.co/95PZlv7tB6 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kò sí ènìyàn kan tí kò gàn èyí bí a ṣe ń ja ogun jáde. Pàápàá àwọn òṣìṣẹ́ sinimá tí kò sanwó, tí ń rẹ́ẹ̀rín. Ìríra! | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
ẹni tó ńsáré tó ńwo ẹ̀hìn ó di dandan kó fẹsẹ̀ kọ whoever keeps looking back while running will certainly stumble ignore distractions stay focused | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#TranslateToYoruba awon oro bii Blackberry,Facebook ati Twitter ko see tumo si Yoruba nitori oro akanse fun ile ise (Trademarks) ni won | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Omi tuntun Nàìjíríà. . Mo gbádùn fíìmù yìí gan-an ni o! Ògidì ni, kò sí irọ́ níbẹ̀, ó pani lẹ́rìn-ín, ó sì tún ń wádìí àwọn ohun tó ṣe kókó lọ́nà tó tọ́.. . Mò ń fojú sọ́nà fún eré míràn tí Abba yóò kópa nínú rẹ̀. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: Kilode Ti Ogbeni Bukola Saraki Fi N Paro?: O paro Nile Ejo Tiribuna, O Tun Paro Fun Omo Naijeria: Ni ile Yorub... http://t.co/0… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ààbò Olórun á dájú lórí wa lósùyí ní orúko Jésù. #newmonth #Naija #yoruba #ijesha #February2021 #ValentinesDay | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Àmín àṣẹ. Adùn oyin náà á kárí o. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìyá rere ni ìyáà mi. Ẹ ṣeun ùn mi màámi, Èdùmàrè á san yín lẹ́san rere nítorí iṣẹ́ ribiribi tí ẹ ṣe. #AyajoOjoIya https://t.co/ocvk2kOniq | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó dàbí wípé wọ́n mànánmàn ṣe fíìmù yìí láti kàn dá àyà já àwọn olùwòran ni. O jẹ sinimá tí o dun ni láti wò. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Orúkọ mí ní Olùwashinà, ọmọ ìlú Èko ati Ifęwará ní mí ní Ìpínlẹ̀ Osun. Èko ní won bimi si. Iyà mi wa lati ìlú sokoto🤣#TweetInYoruba 😂🤦🏿♂️ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọrẹ orisirisi lo yi ọ ká sọra fun aye ọrẹ mi ẹni ti o ro wipe kò le dà ẹ iru wọn ni ma n seku pani | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
orúko mi ni tolulope ọmọ ogunleti ọmọ bíbí ìlú lanlate ni ìpínlè ọ̀yọ́ojúlówó ọmọ yorùbá ni mo jemo nifẹ si dodo lọpọlọpọ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bóyá ìrònú nkan tó ń ṣẹlẹ̀ nílé ò ní jẹ́ kí àwọn ọmọ Mali ó ṣe takun-takun tó. Ọ̀rọ̀ burúkú tòun tẹ̀rín. :D #Afcon2013 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
a yó rí òmíràn gbà | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kìí ṣe orúkọ òbí, ní a fi ń wo àwọn ọmọ ẹbí kan ní Ilẹ̀ Yorùbá, bí kò ṣe orúkọ ẹbí tàbí agbo ilé tí àwọn ọmọ náà ti wá. Ní apá òmíràn ẹ̀wẹ̀, ẹbí lè jẹ̀ẹ́ àwọn ọmọ ìdílé kan, tí wọ́n ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú ẹbí òmíràn nípa ìgbéyàwó, àgbàtọ́ tàbí ìtẹ̀dó. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ègún ìdílé lè jẹ́ àfọwọ́fà bí àwọn nǹkankan bá tasẹ̀ àgèrè, tí ohun gbogbo ò lọ sòsé, gẹ́gẹ́ bí ó ṣe yẹ kí ó máa lọ. #OgunIleAye #EgunIdile #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ kú ọjọ́ mẹ́ta o! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.