text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
Ìtàn yí kò já fáfá láti ìbẹ̀rẹ̀ ṣùgbọ́n má jẹ́ kí ó sú ọ. Ìtàn gidi gbáà ni.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ọ̀kan nínú àwọn eré tó bàjẹ́ jù tí mo wò.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Oun a ní kí òkóbóo wọ́n bọ̀, wọn ò bọ̀ ọ́, wọ́n lá wọn lè bọ igbaa abẹ́rẹ́. #NationalConference #SocialMedia
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Chelsea ti fi owo osi juwe Ile fun akonimoogba Roberto Di Matteo, leyin ti o fi idi remi pelu ami ayo meta, ni orileede Italy lanaa
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
🇳🇬🇳🇬🇳🇬Ojo eni ni 👇Oya e ba wa da si 👏👏👏👏👏🎬🎬🎬#YorubaTweetDay #YorubaTweetDay #YorubaTweetDay #YorubaTweetDay #YorubaTweetDay #YorubaTweetDay https://t.co/LeKwJFsF9Q
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
yorùbá words and their english equivalents frustration pin lẹ́ẹ̀mí depression ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn horny ara gbẹ̀kan competition ìdíje excursion àbẹ̀wò sí ibì kan cave ihò àpáta discuss jíròrò righteous òdodo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user :-D e gbayi jare. nko mo wipe awon eniyan ti won feran KSA wa lori ibiyi
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Olóyè aàfin Ọba Bìní fi kún ọ̀rọ̀ rẹ̀, ó ní kò sí Aláṣẹ ìlú t'ó ń jẹ́ ọba lẹ́hìn #Benin. #YorubaBenin
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹ yáa wí bẹ́ẹ̀. Àpèmọ́ra eni làá pe tèmídire
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ́rin lọ́nà mẹ́rin - 4 in 4 places - 4⁴ Ìdámẹ́jọ - ⅛ CURRENCY /OWÓ Ogójì owó - 40 cowries - 1 string Igba owó - 200 cowries - a bunch of 5 strings Ẹgbẹ̀wá owó - 2,000 cowries - Head (10 strings)
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orisa bi iya o si laye ojo to ba le iya kii yani iya loosa ti n gbeni ti kii gbebo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user ọ̀pẹ́lẹ́ngẹ́ ṣubú l'àwo!
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ile tomo wa loni ojumo ire ni,ona si ona la ojumo ire ni RT @user: Ojúmọ́ ire o.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó ku ọjọ́ Méje! Fi iṣẹ́ rẹ ránṣẹ́ sí wa. You can be the next #LawuyiOgunniran 😀 Wo https://t.co/tQJihRMGO1 fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé. #AtelewoPrize #Yoruba #Atelewo https://t.co/Lo6kHQSJbH
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#iroyin, #yoruba, Eyi ni itan igbesi aye Olowogboyega, olori osise ijoba tuntun l'Osun… https://t.co/1RAq3OROIx
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nílẹ̀ O'òduà, ẹlẹ́ṣẹ̀ yó sanwó ìtanràn, bí kò bá lówó, yó di ìwọ̀fà tí òmìnira wà fún bí ó bá ti ṣiṣẹ́ fún iye àkókò díẹ̀. #RememberSlavery
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ibadan Omo Ajorosun: Ohun To Ye Ke e Mo Nipa Ilu Ibadan https://t.co/EzghdiZIB0 #Oniroyin #TweetYoruba #Yoruba #Oluyol…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó sẹ́ kù sí ibì kan. Ẹ̀rọ. Àìlọ́gbọ́n. Ní òtítọ́ sísọ.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ní ìparí, ẹ jẹ́ kí á máa ṣe ara wa lẹ́ṣọ̀ọ́, kí a máa fi ìgbàogbo dùn ún wò, nítorí a ì í ṣe é mọ̀. Ẹ jẹ́ kí á máa rántí wípé 'ìríni sí ni ìsọni lọ́jọ̀'. #Alaye #Yoruba #IrinisiNiIsoniNiOjo #Owe #LearnYoruba #Language https://t.co/ZHVBTfb86j
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Nje o le so die nipa ewi ojogbon Adebayo Faleti ti o ti ka ri?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Oya eje ki ako ija igboro lo ba @user Oya eko ada, kunmo, ake ati ibon shakabula ki a lo tu @user sile. Oga @user eni ba je gbi, lo ma ku gbi, ele lo ba Fayose sewon, iyen o kan enikeni. https://t.co/aYr9T2luOM
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Akọ jẹ̀díjẹ̀dí ní í máa ń fa kí ìròbo ìdí máa yọ. Àwọn kan gbà pé iṣẹ́ abẹ ni ọ̀nà àbáyọ sí ìròbo tí ó bá yọ, àmọ́ kò le tó ìyẹn. Kókódu àgbọn, ọkọ̀ ataare àti ọṣẹ dúdú láá kì í wọlé láàárín ọjọ́ 4. Má jẹ̀ẹ́ kí wọ́n gé ọ ní fùrọ̀ o! #Yoruba #Ewe https://t.co/G4qP3dwTD5
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Yàtọ̀ sí ajá Ògún tí a pa, a tún ń fún Ògún ní iṣu, adìẹ, epo, iyán, obì, èwó pupa àti funfun, àti ẹmu. #OsuOgun #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àpèmọ́nraeni làá pe tèmídire. Tèmídire o!! #adura
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èmi ọmọ Oòduà atẹ̀wọ̀nrọ̀ ni nkí yín o. #ekaaro
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Afi igba ti awon ara Ilorin fariga fun @user kaka ki wan so oko fun asetani Saraki ni won paruwo ole! ole mo https://t.co/EcznacGVca
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: A kì í fi ojú ọwọ́ ṣiṣẹ́ tán, káa tún wá fi ẹ̀hìn ọwọ̀ dà á nù. / Never destroy with your backhand what your open hand…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí a bá ní 'nǹkan àìrí', èyí ṣe dédé ohun gbogbo tí a kò le è fi ojú rí, àmọ́ tí a nígbàgbọ́ wípé ó ní àṣẹ nínú. #Asairubo #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user oni, Ojo kerindinlogun, osu kokanla, egberun odun meji ati meedogun... Se mo gba?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ Káalẹ́ o ọmọ Yorùbá! Ẹ sì kú ọrọ̀ Ajé.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
gbogbo ẹni tí ìlọsíwájú ètò ilera jẹ lógún ẹ fọwọ́ sí ẹ sì tàn án ká sí àwọn ọ̀rẹ́ yín náà cc
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Aṣọ wa ò ní fàya o, àwọn tí kòì tí ì ní aṣọ láyé yóò ti ọwọ́ àlà bọ osùn fi pa ọmọ lára láṣẹ Èdùmàrè. #AyajoOjoAwonEwe #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Odù Ifá Ọ̀yẹ̀kú Méjì, ẹsẹ̀ 'kíní fi ọfọ̀ sọ nípa obì - """"""""gbogbo aláwẹ́ obì ni ikú í pa, ọ̀tọ̀ ni à á yọ oofúà obìí sí"""""""". #Obi #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kileleyi aunty se alafia le wa sa eleyi okin se oju lasan o ewo ni ki adelebo ko si hijabu ma fi ja ese kiri oga o
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eérú kọ́ ni ìdáhùn sí ìbéèrè yìí ọṣẹ dúdú ni bí ọṣẹ dúdú bá rí omi odò á hó bí ó bá sì hó a di funfun
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọlọ́run KKó ṣé ún tí. God's Probability is always 1 #iyil2019 #indigenouslanguage2019 #africa #culture #nigeria #yoruba #igbo #hausa #ghana #gbajumoÒṣeré… https://t.co/chrhs6Q68s
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìsòro ni ó fa àwọn oníìwé-ìfiránṣẹ́ lórí wíwó pẹ̀lú ohùn-lórí àti òtítọ́ àti búburú àyípadà nínú àwọn kíkọ́ 'ìhùwàsí nípasẹ̀ àwọn eré náà.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ẹ kó owó wa padà. Hán! hán! kílódé, ẹ fẹ́ jẹ wá run ni. #OwooWaDa #WhereIsOurMoney
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí èèyàn bá ṣèṣì kọ Ìkọkúkọ sórí àwòrán Ààrẹ ní Burundi, yóó bá ara rẹ̀ lẹ́wọ̀n ni. Burundi: Kọ Ìkọkúkọ sórí àwòrán Ààrẹ — kí o wẹ̀wọ̀n https://t.co/sLrTM7eYRi via @user
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
dẹ̀dẹ̀ níi rọ kókò lágbàlá àṣẹ olúwa ni ara á tù wá lọ́dún yìí ẹ̀ bá ṣàmí ọdún tuntun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ÒWE / PROVERB Ìlọrin ò lóòṣà, ẹnu lòòṣà Ìlọrin TRANSLATION: Ìlọrin person has no deity, his/her mouth is his/her deity. ÌTUMỌ̀/MEANING: Ẹnu lásán ni ẹni báyìí gbójú lé / the person in reference has no substance but, only word of mouth.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìjì tó jà tó kó aṣọ ní yàrá, ẹni tó wọ tiẹ̀ sọ́rù kó má ṣàfira o"""""""". Òwe àwọn àgbà Yoòbá ni. #BokoHaram
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Egbé, Kánàkò àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ t'ó jẹ́ṣẹ́ ọpọlọ àwọn baba wa ńkọ́! A ní kí ní ń jẹ́ sáẹ́nsì? Oògùn ni yẹn àbí kì í ṣe science. #Kiwontode
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
lẹ́yìn ìwádìí oṣù mẹ́ẹ̀ẹ́dógún ọ̀pọ̀ èèyàn ló ní iná mànàmáná ti mẹ́hẹ ju tẹ́lẹ̀ lọ
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Haha. """"""""Gbe s'ori mi"""""""". Sho ra ree ooo. #learnyoruba #yoruba #Duolingo https://t.co/reU5RFojIK
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bóyá ó súnmọ́ kókó-ọ̀rọ̀ náà láti sọ pẹ̀lú mímọ́ tí ó ń béèrè.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Bí ó bá gbẹ dáadáa tán, ó di ilé ẹ̀rọ láti já a. #iya #elubo #isu #ounje #yobamoodua
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Bó ti rí gẹ́lẹ́ nùu arábìnrin wa.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#Atunko: Èrè lọmọ ọlọ́jà ńjẹ, èrè la ó jẹ níbi ọjàa wa, gbogbo wa la ó jọjà ọjà ò ní jẹ wá o. #OjoOloja #Lagos @user
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
fún bí ọgọ́rùnún ọdún méjì sẹ́hìn ọmọọba ní í gun orí àpèrí aàfin olú
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mo ti jẹ orógbó kóhùn le gbó mà á gbó gbó gbó bí àjágbó ṣe gbó
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọlọ́run má jẹ́ a r'ogun ní Nàìjá o! Ogun ò kí nṣe nkan kékéré o!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìjàmbá nlá gbáà ni fún bàbá trump àyàfi kó gba ònàa pápá golfu lọ kíákíá kó lọ mu omi sùúrū díẹ̀
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
aworan aare nijeria dokita jonathan ati aare ano ogagun mohammed buhari ni ilu abuja fun ajodun asepo amunisin
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
oruko mi ni hassan adebayo akanbi omo jagun omo ago ishona ni ilu oyo alaafin e kaaro aku ola jimoh
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Owó ní b'óun ò bá sí nílé, k'ẹ́nikẹ́ni ó má dá àbá kankan lẹ́yìn òun. I am very much interested, if you have any informatio…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹni mélòó ló mọ̀ ọ́ láṣà ní nàìjá àwọ̀ wo ni wà á mú bí a bá ní o mú ẹyin ọjọ́ àjíǹde tí o fẹ́ràn pupa ni mo fẹ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gbóyà = brave (Tọ́lání gbóyà gan-an - Tọ́lání is very brave) #InYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ja lolo ja lolo♫♫*K1voice*""""""""@user: ♫ Èrò ọjà olówó ... ♫ #BringBackOurGirls""""""""
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
sínsin òkú sí ilẹ̀ìsìnkú lòdì sí àṣà yorùbá ilé ni wọ́n ma ń sin òkú wọn sí yàtọ̀ sí àwọn òkú abàmì tàbí òkú tí kò yẹ ní ìtòsí ilé tí wọ́n ma sin sí ibòmíràn àwọn ẹlòmíràn lè yan ibi tí wọ́n fẹ́ kí wọ́n sin wọ́n sí tí wọ́n bá ku
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
BBC News Yorùbá - Ìsúná Inec: N1.79bn làwọn agbẹjọ́rò nìkan yóó gbà https://t.co/F4TIZ9yzMr
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ yẹ é fi ẹnu tẹ́ ìṣẹ̀ṣe àti àwọn oníṣẹ̀ṣe. Ọ̀kan l'Olódùmarè, ọ̀kan nílé ayé, ọ̀kan lẹ̀sìn, ọ̀nà ló pọ̀. #Iseseday #Iseselagba #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo wá ní ṣebí ara iṣẹ́-ọwọ́ọ """"""""""""""""ọ̀gá àgbà amúnisìn"""""""""""""""" ni. Wọ́n kò po ìpara arabíbó pọ̀ f'éèbó, ẹnidúláwọ̀ ni wọ́n ṣe é fún. #Kemika
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: emi """"""""@user: Ó yá o! Ta ló tó gbangba sùn lọ́yẹ́ láì faṣọ bora, kí ó dáhùn ìbéèrè yìí »»» #Ibeere""""""""
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
haha ẹṣeun lágbára ọlọ́run tó bá dénú ire ni yó ṣe
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ehín erin = ivory (ọ̀gbẹ́ni Philips àti ikọ̀ rẹ̀ jí ehín erin Ìbíní ➡️ Mr Phillips and his team stole Benin's ivory) #InYoruba #learnyoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn ọkùnrin ilé tí wọ́n jẹ́ àgbàlagbà ilé, tí wọ́n sì ju àwọn òbí ẹni lọ, """"""""""""""""bàbá àgbà"""""""""""""""" ni wọ́n ma ń pè wọ̀ọ́n. Àwọn obìnrin ilé, tí wọ́n kéré sí òbí èèyàn, """"""""""""""""ìyá kékeré"""""""""""""""" ni a má ń pè wọ̀ọ́n. Àwọn obìnrin àgbà ilé, tí wọ́n ju òbí ẹni lọ, """"""""""""""""ìyá àgbà...
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àjọṣe wa ò ní bàjẹ́ o @user @user @user @user @user @user @user @user #2014WasGreatBcosOfU
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user Awon ti won ta #Yoruba ni opo olorun ma da ejo won.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
* ìgbá, igba, ìgbà * #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àmọ́ olè iná tó kú níjọ́sí ṣèbí olè eérú ló fi bojú àbí jàndùkú ọ̀gẹ̀dẹ̀ tó kú níjọ́oníìí jàndùkú ọmọ rẹ̀ kó fi rọ́pò ni
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: 14. Ǹjẹ́ o lè sọ orúkọ òkúta inú àwòrán yìí 👇? #Ibeere #Yoruba https://t.co/otfuITJSdO
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ni olóòlàijù ni àjànàkú tí í migbó kìjikìji ni ẹranko àmújàgan
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àwọn ọmọ wa gbìyànjú wọ́n fakọyọ àmọ́ ṣíṣe sì kù
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
13. Poison ni ọ̀hun lédèe Yorùbá, acid ni___ #ibeere #Yoruba #learnyoruba #language
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Mo ki gbo gbo awa omo Karo Oji ri, ki apejo #TweetYoruba ko san wa si ire, owo, omo, alafia. Ki afefe ife, afefe ayo o fe s…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹgbẹ́ àti ìtẹ̀wé ìṣọ̀kan Yorùbá, jákẹ̀ jádò gbogbo ilẹ̀ Yorùbá, Òkè Ọya àti Òkè Òkun. Orísun ìmọ̀ yìí: Adebanji Akíntóyè (2014), A HISTORY OF THE YORÙBÁ PEOPLE, Amalion Publishing, Dakar. Abala 360
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ ṣá ṣe ẹ̀tọ́ọ yín fún kete #Ekiti, kí a lè lẹ́ ẹ ṣe bẹ́ẹ̀ ṣe sọ pẹ́ẹ ó ṣe. @user #Fayose
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Oorun kò kojú, bẹ́ẹ̀ l'orí ń laago. Èmi nìkan ló yé, kò le è yé wọn. #TaLoYe
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọpẹ́ ńlá lọ́wọ́ aàrẹ àkọ́kọ́, ọmọ Ibo, Olóyè Benjamin Nnamdi Azikiwe fún'ṣẹ́ takuntakun gbogbo. #Independence http://t.co/yEITW08P9e
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀pọ̀ ló fẹ́ dọjọ́ òní àmọ́ ikú ti múwọn lọ. Ṣùgbọ́n Ọlọ́run Ọba múwa wà láyé. Ọpẹ́ ni fún Olú ọrun. #ekaaro
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ilà ọwọ́ tèmi rè é. Ọba Adẹ́dàá l'ó kọ ọ́. Báwo ni ilà ọwọ́ tì rẹ ṣe rí? https://t.co/iknbFHqfwH
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user @user Wò ó, orí ẹ pé bí aṣọ gbági fún èsì tí ó fún àfá yìí. Ó dùn mọ́ mi nínú porogodo 😁
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Shangba fo! #TweetinYoruba Ogbeni @user ja no, Amofin @user ba ko lu pelu oko bolekaja. https://t.co…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìpasẹ̀ oníṣòwò mùsùlùmí l'ẹ̀sìn Ìmàle fi wọ ilé sí wa lára. A bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ kéwú; ìmọ̀ kíkà ní ń jẹ́ kéwú lédè Larubawa. #nigbatiwonde
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wonderful life. . . .👉 Yorùbátv ẸGBẸ ỌMỌ OLÚWA BÍ GBOGBO ÀGBÁYÉ Ojú òpó ìkànsíraẹni 🇳🇬🇹🇬🇧🇯🇧🇷🇨🇴🇨🇺🇬🇭🇨🇮______________________________□ Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba #yorubatv #yorubaweddings #ebi #asoebi #nigerianwedding… https://t.co/Y9UKYSXNfs
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn olólùfẹ́' kò ní èyíkèyí àtilẹ̀bá, ǹkan tàbí ìrònú.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ire lójú owó ń rí. Ire lobìrin ń jẹ lérè ọjà. Ire ni un ó máa rí lọ́jọ́ 'ogbo. Àṣẹ Ire! #Iwure
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọmọ adú ló ṣe àpò ìgbé ẹ̀jẹ̀ pamọ́ sí ìyẹn blood bank ní èdè gẹ̀ẹ́sì
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bẹ́ẹ̀ náà ni mo jáwé gbégbé, gbogbo ibi tí wọ́n ní n kò gbọdọ̀ gbé ni mò ń gbé. #Ayajo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
À ń pariwo wípé kò sílọsíwájú, àfi ìwé l'ómi adágún tàbàtàbà bí alákàn látorí ègún tí ó ń bá ọmọ adú-lójú fà á. #OgunIleAye #EgunIdile #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
epo ńbẹ ẹ̀wà ńbẹ o epo ńbẹ ẹ̀wà ńbẹ o àyà mi ò já ó e àyà mi ò já láti bíbejì o epo ńbẹ ẹ̀wà ńbẹ o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọmọ èèrá kún agbọ̀n hà re è è è kó bá rí i kó wò ó fìrì
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
o wa di bi omode ba gbon ogbon kiku ki iya re gbon ogbon sinsin efon fe gba ijoba eewo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àsìkò ìdá ara wò. Ìlú àti ìpínlè wo ni ère yìí wa ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ẹ̀bùn rán pé wà fún ẹni àkọ́kọ́ tí ó bá gbà á. #OrílèèdèNàìjíríà #Yoruba #EdeYorubaRewa @user United Kingdom https://t.co/8w3v5qdLEb
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọfẹ́ ni béèli ni ago ọlọpa orilẹede nigeria ti wọn ba beere fun owo epe jọwọ efi eyi han ẹnikan lo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀rọ̀ yìí yó lẹ́yìn o, ẹ lé omi Olókun kúrò níbi Aṣẹ̀dá dá a sí. Ìbínú Olókun ò sì da #Ilubirin http://t.co/8WRLlaBpKw
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mansa musa ẹ kú ajálẹ́ o ẹ jọ̀ọ́ ṣé mo rí wúrà díẹ̀ mo ní ṣíṣe kan lọ́jọ̀ àbámẹ́ta ńjẹ̀bú
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Sínsin òkú sí ilẹ̀-ìsìnkú lòdì sí àṣà Yorùbá. Ilé ni wọ́n ma ń sin òkú wọn sí, yàtọ̀ sí àwọn òkú abàmì tàbí òkú tí kò yẹ ní ìtòsí ilé, tí wọ́n ma sin sí ibòmíràn. Àwọn ẹlòmíràn lè yan ibi tí wọ́n fẹ́ kí wọ́n sin wọ́n sí, tí wọ́n bá ku
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wọ́n ní ká lo onírúurú èlò ti wọ́n pèsè fún ìlò onìròhìn láti fi pín àwọn ohun àṣà iṣe ìbílẹ̀, ìpínlẹ̀ àti orílẹ̀-èdè wa #Google #journalism
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train