text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
Kí la npe oṣù kọkànlá ọdún ní èdè Yorùbá? #ibeere
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Bí ọkọ̀ kan ó re Ejìnrìn, ẹgbẹgbẹ̀rún ẹ̀ á lọ. / If a bus won't go to Ejìnrìn town, thousands others will. [Alternativ…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
.@user ti wa di alagbafo fun @user lori oro ibo egbe @user ni ipinle eko. Ogbeni @user ati Gomino @user yio fi igba gbaga ni ojo keta, osu kewa, odun 2018 https://t.co/93q0MqLQZV
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí a tó bẹ̀rè oun-kóun, ẹ jẹ́ ká fi ti #Olúwa síwájú.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Àwọn Ìtálì ti sọ àwọn ará ìlú Ọba d'ẹrú o... Sàká àti àwọn ẹmẹ̀wà rẹ ti fi ọwọ́ òsì júwèé ilé popsy wọn. #Yoruba #EURO2020
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wọ́n ń pè ọ́ ní 'Ládì', inú rẹ̀ ń dùn! Àbí ara obìnrin t'á ní 'ẹsikús mi ama Lady' ni ọ́! Bẹ́ẹ̀ ò sì mọ ìtumọ̀ lady tí o gbé karí ọ̀hún.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ní nkan bíi ẹgbẹ̀rún kan-àbọ̀ ọdún sẹ́hìn, àwọn ọba mùsùlùmí láti ìhà aríwá Afirika mú ìdàgbàsókè bá #Rhonda. http://t.c…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Shilling rọ́pò owó-ẹyọ, a bẹ̀rẹ̀ síní fi Ṣílè méjì (2s), Ṣílè kan (1s), àti 6 pence ṣe káràkátà. #OwoEyo #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ọ̀bẹ bàbá bọ́... #InYoruba #learnyoruba #Yoruba #language https://t.co/E8X3yWtPVr
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àgbà kìí wà lọ́jà kórí ọmọdé wọ́ ẹ jẹ́ kí a jọ ti apá ikú ọmọ ìkókó wọlẹ̀ ní
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
It makes a world of difference when God deliberately favors you. This week, you'll enjoy the favor of God. Ìyàtọ̀ wà láàárín kí ènìyàn máa lé olóore ká àti kí Ọlọ́run mọ̀ọ́mọ̀ fi ojú ire wo ni. Nínú ọ̀sẹ̀ yìí, a ó bá ojú rere Ọlọ́run àti ti Ènìyàn pàdé. #yoruba https://t.co/GaJ8bAj9Cg
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bíkòṣe ìyànjú òyìnbó láti pa iṣe wa run, pẹ̀lú ètò tí yóó mu wa gbàgbé àṣà baba ńlá wa. #kojoda #yorubacalendar
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Tí ọ̀rẹ́ kan bá ṣubú, èkejì á sì fàá dìde. / If one friend falls, another ought to pull him up. [Lending a helping ha ...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
e daagba e fowo pa ewu isu oma a jina fun yin je eku ase oni oo°˚˚˚°
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ wá o. Gbogbo rògbòdìyàn tí ń lọ ní òke-Ọya yìí ti sú èmi o. Ọgbọ́n wo la fẹ́ dá sí i báyìí o? #BokoHaram
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ ṣọ́ra fún ayédèrú oyin o. Mo ti sọ ńpa 'ẹ̀ rí.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Happy birthday to you @user. Àṣèyí ṣàmọ́dún láṣẹ Èdùmàrè
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Oruko amutorunwa nko? Omo ti a bi ni ojo isegun https://t.co/gUsMj5zZf2
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
15. Ọbẹ̀ tutù tán adámú ḿbù ú lá. Kíni ìtumọ̀ òwe yìí àti pé irú èèyàn wo ni à ń pè ní adámú? #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
gbogbo eniyan ni a bi ni ominira iyi ati eto kookan si dogba won ni ebun ti laakaye ati ti eriokan o si ye ki won o maa huwa si ara won gege bi omo iya
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ede yoruba eye ijebu mo ki dede wen dede ewen omo naijiria tonti oluku re translation yoruba language ijebu language i greet you all all nigerians and her friends
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ojumo rere lo mo wa gbogbo omo oodua
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹṣin ọ̀rọ̀ ní bí a ò bá rí àdán a ó fi òdẹ̀ ṣẹbọ ǹjẹ́ ìyàtọ̀ wo ló wà láàárín àdán àti òdẹ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọkọ̀ tèmi ò ní forí sọgi láíláí lágbára ọlọ́run ti yín nkọ́ temi na o ni fori sogi lagbara oluwa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ikú má pawo mọ́ o, Ikú ti yẹ̀ lórí awo; Ọ̀tọ̀ ni à á ya oofúà obìí sí. Ikú mọ́ pawo mọ́ o, Ikú yẹ̀ lórí awo.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Buhahaha""""""""@user: Lo dabi eni ti o ti pe omo Ogoji odun RT """"""""@user: Oni ni Carlos Tevez agbaboolu omo Argentina pe omo odun mo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ojú ayé tí ó fi iga gbà ga pelu ìṣe burúkú. Ṣùgbọ́n idojuti ni pé a ti nkan ti o ni ìtumò ṣùgbọ́n tí kò fa imunisin gẹ́gẹ́ bí ohun búburú àti àtẹ̀yìnwá tí ó ṣẹlẹ̀ nígbà tí wón kó àwọn àgbègbè yí ni pápá mọ́ra
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Hmm!Oba aseyi owu, """"""""@user: Ọlọ́run tóbi lọ́ba. Ibi tí àwọn kan ti nlàágùn nítorí ooru ni àwa kan ngbọ̀n tìtììtì ...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Allahumma isrif 'annal-waba-a-wal bala-a"""""""" Olóhun Oba ò, gbé àjálù àti àdánwò kúrò fún wa Oh Lord! Drive Calamities and catastrophes away from us. (Aamin) #JummaMubarak #MuslimsConnect #MuslimTwitter #Yoruba #Ramadan #Lightmealsahur #ibadantwittercommunity #Muslimah
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ogoji eniyan ipinle taraba ni o fi ara pa ni bi ija elesi mesi
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọ̀tọ̀ lorin tí à ń kọ níbi ṣíṣe ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni ìlù tí à ń lù náà níbi ṣíṣe pẹ̀lú
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Modúpẹ́ lọ́wọ́ọ yín pé àjọṣe wa láti ọdún kan sẹ́yìn sì ń gún régé, á tú bọ̀ máa dára síi ni. #yobamoodua #odun #kan #lori #ayelujara
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ahọ́n màlúù a máa dùn yùngbà yungba😋
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Hahahahahaha, @user je ki n rerin igba kekere e mi loni
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
10. A. Ìran Yorùbá wo ni à ń pè ní Òṣómàáló? B. Kí ni ìtúmọ̀ Òṣómàáló? #ibeere #Yoruba #learnyoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Mo júbà o. Ẹ kú ìpolongo àṣà wa f'áráyé. Kò ní tán níbẹ̀ o. Ọwọ́ gẹngẹ ní ń ṣíwájú ijó. Aṣíwájú ni yín ẹ kò ní di èrò ẹ̀yìn.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user a dupe pupo. Mo se amin adura fun emi ati eyin naa.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí ni▶️ Ìdíje Ìbéèrè Àti Ìdáhùn Lédèe Yorùbá Níbo▶️ Ọ̀tà (Ìpínlẹ̀ Ògùn) Lọ́jọ́ wo▶️ 19 oṣù Òkúdù ọdún-un 2018 Nígbà wo▶️ aago mẹ́wàá òwúrọ̀ #Yoruba #quiz #IYIL2019 https://t.co/4QMTiKI5pT
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Daada l'Oga Bello wa o. Nbe l'alaafia (in thick Ilorin accent) :D
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
toò èmi faramọ́ ọn ṣá o ṣé ti ibi à ń gbé làá ṣe ẹ máa rọ́jú
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
èdèe wa ni tiwa ẹ jẹ́ a gbée lárugẹ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user. Hmm! Ope ni f' Oloun. Eledua ko nii fi ebi pa enikankan ninu wa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
a pè wọ́n wá jẹun wọ́n mú wa lọ́wọ́ dání wọn kò jẹ́ ká jẹun
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ki bata lese bawo?😂😂 Shey owa OK sha? 🐢 Ma shepe fun kabiesi oo. """"""""ki bata pelese #yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹwà èdè Yoruba. Can you form a sentence with these four words? - Àpáta = Rock Alapata = a butcher Pátá = pant Àpáta= a name answered by some people e.g. @user @user @user #yoruba #yorubatradition #culture #soedeyoruba https://t.co/2VErIDsgl2
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ajo kindun ki odidere eye oko gbagbe ile ilé làbọ̀ ìsinmi oko
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ẹ jẹ́ ka pọ́n àwọn ìyàwó wa, àwọn ìyá wa, àwọn ọ̀rẹ́bìnrin wa, àwọn ọmọgé, àwọn sísí, àwọn màmámàmá wa ,àwọn ọmọbìnrin ...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bọ́la yó ṣe rí ònìí la yó ti mọ̀ ìbò ọdúnun ǹjẹ́ báyìí náà kọ́ ni yó ṣe rí ìjọba màdàrú
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ÀBÀJÀ ÀWỌN BAṢỌ̀RUN Irú ìlà àbàjà yìí ni àwọn Baṣọ̀run Ọ̀yọ́ ma ń kọ, láti fi dá wọn mọ̀. Wọ́n ma fa ìlà mẹ́ta láti òkè wá sí Ìsàlẹ̀, ní ẹ̀kẹ́ kan. Ìlà mẹ́ta lọ sí ẹ̀gbẹ́ ní ẹ̀kẹ́ kejì. https://t.co/DUIXHwiQtp
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ̀jẹ̀ ibi awọ fẹ́lẹ́ ojú-ìgó; #ibale tí yóò ro sórí aṣọ àlà tí a tẹ́ sílẹ̀ ni yóò dúró gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rí sí ìdílé ìyàwó. #ibale #Yoruba #Asa
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré rádaràda pátá́ gbáà ni.. . Kò tilẹ̀ ṣe é máa sọ,réderède, ráunràun, òṣì rata má rayọ̀.. . Kí ni wọ́n tilẹ̀ ṣe sinimá yìí gan fún ná?!
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Gbogbo ọ̀rọ̀ ló lésì, ṣùgbọ́n kì í ṣe gbogbo ọ̀rọ̀ làá fèsì sí. / There is always an appropriate response to every statement, but it's not every statement that one responds to. [Not all issues deserve our attention: be focused; ignore distractions.] #Yoruba #proverb
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Orin Ẹ̀yẹ Ilẹ̀ Olómìnira Nàìjíríà Dìde ẹ̀yin ará Wá jẹ́ ìpè Nàìjíríà ká fi fì ìfẹ́ sin Ilẹ̀ wa Pẹ̀lú òkun àti ìgbàgbọ́ Kí iṣẹ́ àwọn akọni wa Kó má ṣe já sásán Ká sìn ín tọkàntọkàn Ilẹ̀ tó lómìnira àti àlàáfíà Sọ́ di eyọ̀kan #naija #yoruba #oroyoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí a bá yan ẹràngbẹ́ lójú ààrò, gbogbo omi burúkú inú rẹ̀, títí kan kòkòrò afàisàn àìfojúrí t'á a kò lè fojú rí ni yóò bá iná lọ. #Ebola
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
2. #Parioweyii À rí ìgbọdọ̀ wí... #Ibeere #Yoruba #Owe
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
“@user: @user : eku ise o,eko o ni baaje!” Èkó Àṣẹ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: #TweetinYoruba Oruko temi ni Omoyungbo Toyin, omo Oka Akoko ni mi. Abi mi si Ikare ni ipinle Ondo. Ise Ologun ni mo n se.…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
iyì àṣà èdè àti ẹṣin abalaye yorùbá ni orileede brazil pẹlu
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọjọ omi àgbayé lòní o. Omi o ni gbé wá lọ o. #ekaaaro #WorldWaterDay http://t.co/Cls9ZuGEub
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Se apejuwo ara re ni ede Yoruba. Oruko temi ni Ogbeni OluwaKayode RAFELU omo Ogundamisi omo abinibi ile Yoruba ni mi mo ...
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ayé dí wọwọtìwọ ayé dí wọ̀wọ̀tiwọ̀ ǹjẹ́ ta ni yóò lànà fáyé o ògún lànà fejubọ̀nà títí lọ dé otù ifẹ̀ níbi ojúmọ́ ti mọ́ wá
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé bí ẹni ń forin kíkọ ṣe agbe (tọrọ owó) ni ọ̀ràn náà rí, ni a fi pe àwọn òǹkọrin/olórin ni """"""""""""""""alágbe""""""""""""""""? Àṣàa…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ti oluwa ni o e ku ojumo eni a san sowo ilera ati alafia amin
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eré Nàìjíríà tí ń lọ lọ́ra nípa ìfipá bánilòpọ̀, ìkọlù
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: @user Mo dupe lowo yin oo.... nomba ati netiwooku tii wa ninu apo iranse yin
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìlọṣọ eléèédú ni a tún ṣí sí àwọn wèrè ní oṣù kan gbàko ni a ó ní fi lo iná ta la á ro tiwa fún ẹ gba ni ẹ làjà
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Orukomi ni Ajibola Nurudeen omo Ladipo, Omo won ni ile elesin meta ni ilu Ibadan, eko ni won bimisi, Ibadan ni mon gbe #TweetinYoruba https://t.co/ZOY8DfZlcY
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
tí wo̟n yóò sì rí i pé àwo̟n lo ètòìkó̟ni àti ètòè̟kó̟ láti s̟e ìgbéláruge̟ ìbò̟wò̟ fún è̟tó̟ àti òmìnira wò̟nyí bákan náà a gbo̟dò̟ rí àwo̟n ìgbésè̟ tí ó lè mú ìlo̟síwájú bá orílè̟èdè kan s̟os̟o tàbí àwo̟n orílè̟èdè sí ara wo̟n
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Alabosi ise asewo ti o se fun awon jegudujera oto abi? Sebi awon ole ti o polongo lano lo ba ilu je debi ti awa bayi https://t.co/YeANtJL8pf
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ÒWE ÌKÌLỌ̀ / A PROVERB OF WARNING: Ejò tó múra ìjà, ẹ sọ fún wípé kò gbọdọ̀ gba àárín ìjàlọ́ kọjá. Tell a snake that is prepared for battle, not to pass through the lane of soldier ants.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
15. Eranko wo ni à ń pè ní gbẹ̀gẹ́, olúgbẹ̀ẹ́, tí a tún ń pè ní ẹranko Àgan? A] Ìjímèrè B] Ajá D] Ológbò #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ kú ojúmọ́ o ẹ̀yin ẹ̀dá rere. Ṣ'álàáfíà ni? Ṣẹ́ dáadáa lẹ jí o. #ekaaaro
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó dùn . . eré yìí dùn láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin. eré ṣíse náà dára gáan.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Irinkerindo Ninu Igbo Elegbeje - D.O. Fagunwa https://t.co/HNSRfR8Pqj
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọ Ìkòròdú ni ọ́ ni? @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ̀ka èdè ► ado nanti aje ewi ooo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mo fẹ́ran orin yen
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
lábẹ́ Ọ̀gbómọ̀ṣọ́. Gbọ́n'mi si, omi ò tòó kan ṣẹlẹ̀ láàárín Tìmí Ẹdẹ àti Kakanfò Ọ̀gbómọ̀ṣọ́. Ohun tó fà áwọ̀ yìí, kò fojú hàn. Kakanfò fi Ẹdẹ ṣí Ẹtù tí Kìnnìún kò gbọdọ̀ ma ṣ'ọdẹ rẹ̀. Ni ó bá fi ìjà náà lé Lásinmi, tíì ṣe Balógun rẹ̀ lọ́wọ́, láti
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Láì sùn, láì wo. Alálẹ́ yìí ṣe é l'áṣepé. Kó máà jẹ́ àṣedànù, àfi àṣeyege, àṣeyọrí sí rere, nítorí àṣeyè ni alákàn ń ṣepo, àṣẹ iyọ̀ ni iyọ̀ fi ń já'bẹ̀, àṣẹ òṣùpá ni òṣùpá fi ń mọ́lẹ̀, àṣẹ wáà wáà ni ti ìrèké. Ọ̀ṣẹ́ẹ̀turá gbé e lọ sílé àṣẹ!!!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó yé àwọn adúláwọ̀ tó wà ní òkè òkun dáradára. Ó sọ nípa ìrírí ì mi gẹ́gẹ́ bíi adúláwọ̀ tí kò gbé nílẹ adúláwọ̀ tí ó sì ń gbìyànjú láti wá ibùgbé mìíràn.Fíìmù tó dára.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
E kaaro gbogbo eyin omo Yoruba ni'le lo'ko #TweetInYoruba. https://t.co/ElnfbkIHfW
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọjà Kérésìmesì Jamani http://t.co/pCgfp3SB
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí ò sílẹ̀, kí la ò bá pè nílé-ayé, ṣebí ìgbà ilé dé, la délé ayé? Àbí a ti délé ayé kílẹ̀ tó dé ni?. #OjoIle #Yoruba #EarthDay2015
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Se bí okùnrin (be a man) òrò ìyànjú #yoruba #subtitled https://t.co/XpMJ9rP9hx
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
— tí ó ní akọrin obìrin Destra Garcia àti Patrice Roberts —tí yóò mú ìdíje le fún àwọn ọkùnrin, àti bí àwọn akọrin soca ṣì ń gbé àwo orin tuntun jáde, ìfigagbága Ìwọ́de Ojúnà ọdún-un 2019 ṣì ń lọ lọ́wọ́. https://t.co/l2bCkMXOHk
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kò sí ọ̀rọ̀ kánkán tí ó le júwe irú agbára tí ère yìí ni ati wípé ó ṣe ìrántí oriire tí ó jé láti là ìjà abéle kọjá. Ìtàn àgbàyanu tí ó sọ nípa ìtàn ìṣẹ̀lẹ̀ ni burúkú tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti nípa àwọn ènìyàn inú rẹ.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Bóyá fíìmù tí ó dára jùlọ tó jé tii Áfíríkà ní ìgbà pípẹ́!. . . . Baby Police lalẹ̀ bíi òṣùmàrè ní ìgbà tirẹ̀. Mo le fọwọ́ sòyà wípé fíìmù yìí yẹ ní wíwò fún àwon tí ọ̀kan wọn réwèsì tí ǹkan àsa síì má a ń wù wọ́n
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ìfàsẹ́hìn ni ẹ̀sìn òkèèrè mú wá ìtànjẹ́ ló pọ̀ jù la ṣe takú bíi ẹṣin tó lóun ò lọ mọ́n
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí ni à ń pe ewé igi ilá? #learnyoruba #language #InYoruba https://t.co/KLLfAdP7GP
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
gẹ́gẹ́ bí ẹ ti ṣe mọ̀ igi kan ò dágbó ṣe ẹnìkan kì í ṣe erékùṣù ohun a bá jọ ṣe ló ńgúnrégé ẹ jẹ́ á jọ gbé àṣà yorùbá lárugẹ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
awon ebi anikulapo ti ko i we is ijoba wipe awon o ni gba ebun lai je pe won toro idariji fun as
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọmọ tí a pọ̀n sẹ́yìn
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ẹni tí kò dúpẹ́ ẹgbẹ̀fà, bẹ́ igi dí ọ̀nà egbèje. / Whoever is not grateful for small favours, blocks the path to bigge…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àwọn ará ibí yìí lókè ọya ò jáwọ́ ńnú pálapàla ìlù àpàlàa wọn pa ọmọlọ́mọ lẹ́kún èèyàn fọ́nká lọ́wọ́ àdó olóróo yín
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: #orin E je ka fi inu dindun yin Oluwa olore wa, anu re yi'o wa titi lododo daju daju.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
♫ Ẹ̀sọ̀ pẹ̀lẹ́ láyé gbà, ayé gba jẹ́jẹ́ ... ♫ """"
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bamitale ati Oluwasegun rewon he l'Ondo, oba alaye ni won fee ji gbe - Alaroye
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹnìkan ní kí n tú u palẹ̀ fún òun. Lónìí a óò tú oǹkà wẹ́lẹ́wẹ́lẹ́ kí ó ba yé 'ni yékéyéké. #OwoEyo #Yoruba #Onka #Mathematics #Counting
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
In the spirit of the history of ONÍKÒYÍ OF ÌKÒYÍ, we bring to you, the Eulogy of Ẹ̀ṢỌ́ ÌKÒYÍ (GUARDS OF ÌKÒYÍ) 😊 Ká pìtàn, ká mọ̀ ìtàn, ni ń mú orí wú. Ká wá fi Oríkì lé ìtàn, ni ń mú ara yá gágá. Ẹ fi Oríkì ONÍKÒYÍ TI ÌKÒYÍ gbé ìtàn rẹ̀ lárugẹ 😊 By @user https://t.co/7Mv5JLGFTC https://t.co/geujz8DEuI
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
FÁWẸ́LÌ ARÁNMÚPÈ PẸ̀LÚ ÀPẸẸRẸ: AN ✔️ ẸN ✔️ IN ✔️ ỌN ✔️ UN ✔️ EN ❌ ON ❌ ÀPẸẸRẸ / EXAMPLES: AN - ìrAN, àyÀǸ, ẹrANko ẸN - ìyẸN, nígbà yẸN IN - oyIN, irÍNwó, àrÍNyànjiyàn ỌN - wỌ̀Nyí, ọ̀wỌ́N, pỌ́Nbélé UN - irUN, ogÚN, igÚN abbl
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train