text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
#Yoruba people will say Ileya odun imale #BigBrotherNaijaLockdown2020 #BBNaija2020 #Ozo https://t.co/cxhsc5gZRk | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ise olorun ni kiise eyan gbogbo ohun ti olorun da daradara ni | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Káàsà! Ọlọ́run kúușẹ́. Ọba oníṣẹ́ àrà. Ìdí Àràbà lèyí àbí ìdí Arẹrẹ? Àbí ìwọ́ mọ irú ìdí yìí? 😱 https://t.co/5RsjPdopWB | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ayẹyẹ àjọ̀dún àti ìṣẹ̀lẹ̀ kan tàbí òmìíràn tí a máa ń ṣe nígbà àti àkókò tí a máa ń ṣe é ni a fi sọ àwọn oṣù lórúkọ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìbà làá kọ́ dú Ìbà Akọ́dá Ìbà Aṣẹ̀dá Ìbà Olódùmarè Ìbà bàbá Ìbà Yèyé Ìbà ìyà mi Òṣòròǹgà Apanimáàwágún Mo ríbá mo ríbà Kíbà mi kó ṣẹ Nítorí ti akẹṣẹ̀ ní í ṣe láwùjọ òwú Tèmi ni kó máa ṣẹ ní gbọ̀gbọ̀n òkè Nítorí òkè là á bókè | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
iléèṣẹ́ ọlọ́pàá fi àwòrán àwọn adigunjalè tó pitú ní ìlú ọ̀ffà láìpẹ́ yìí sita ękunręrę iroyin wa ni iléèṣẹ́ ọlọ́pàá | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user èdè Yorùbá parun ti.Awa o ni jẹ ko wọmi, iṣẹ ki o ma parun lawa n http://t.co/uUDs4Nsohq #smwMotherTongue | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àtipé ẹpo tó ṣọ̀wọ́n ló tún fàá kí àwọn èèyàn máa gbé epo sínú ọkọ̀ rìn. Tó fi wá di pé àwọn ọkọ̀ ngbiná lójú títì káàkiri! #Nigeria | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré ọpọlọ, ti o dára fún wíwò. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: Lowe! Lowe! La un lu ilu agidigbo! | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Orí tí mo mú wá sáyé, Ẹlẹ́dàá mi kò ní jẹ́ kó dẹ́rù pa mi. Ẹ̀dá mi máà gbàbọ̀dè, dá mi níre, dá mi lọ́lá. Ẹlẹ́dàá máà sùn! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí á tan iná pa agbọ́nrán, k'á f'ọ̀pá gbọọrọ p'ejò, k'á dìtùfù k'á fi gbọ̀wẹ̀ lọ́wọ́-ọ Ṣàngó; ní ìṣojú-u Mádiyàn lagara-á ṣe ńdáni. #EsinOro🐎 #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹni tí ò bá lè ṣe ìṣèṣe ò tọ́ nípò ọba alayé igbákejì òrìṣà. #Ife #Yoruba #Iseselagba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
😂😂😂😂 Olohun ma se wa ni irin ise ESU #TweetinYoruba https://t.co/3tSu8LzyyL | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Epo; à ń fi epo para gẹ́gẹ́ bíi ìpara. Bí a bá fárí tán láyé àti, àwọn bàbáa wa á fi epo pupa párí, tórí á máa dán sànánàn bí abọ́. #Epo | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
wọn gidi, tí wọ́n fi tún padà wá bá wọn gbé. Àwọn orúkọ òmíràn tí wọ́n tún ń fún wọn ni, Ayédùn, Ṣẹ̀hìndè, Dẹ̀hìnbọ̀ abbl. ÀBÍKÚ: àwọn Yorùbá tún rí àbíkú gẹ́gẹ́ bíi aiyé àtúnwá òmíràn. Àwọn ọmọ tí ẹ̀mí wọn kì í gùn, lẹ́hìn tí wọ́n bá bí wọn, | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ipasẹ̀ ìró ọ̀rọ̀ ni kíkọ èdè sílẹ̀ fi wáyé, ọ̀rọ̀ tí a pè lẹ́nu ni ọmọ aráyé sọ di àmì tí a fi dá gbólóhùn kàn kan mọ̀. #EdeAbinibi #IMLD | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: 36. Ọlọ́run ronú lórí ọ̀rọ̀ náà títí, ó sì wá ọ̀nà láti parí ìṣòro náa títí ayé @user @user @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user Ẹ̀ ń polówó ni àbí kí n la? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#TweetinYoruba Ayinla bi a o reni gbekele ateramoshe eni, ebi ki npagun dojo ale, agbeni gbere wapade oluokun. Ekaro eyun omo Oduua | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Itan yi dara ati wipe o gun sugbon o to be.Won se akopo Eré yi daadaa. Ona to dara re ‘Netflix’.Oye fun iyin gidi. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
ó ní òún lè bọ igba abẹ́rẹ́ wọ́n fi ẹ̀tẹ́ sílẹ̀ wọ́n ń pa làpálàpá ṣíọ̀ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
é jowo ki ni itumo adeboye ati adekunle itumo re a ma ru mi lojuadébáoyè adékúnilé orúkọ ọmọ tí a bí sílé aládé | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
a lá a gba òmìnira àmọ́ a ò tí ì bọ́ lọ́wọ́ ọ̀gá ó dìgbà tí a bá fi ti wa ṣe la tó máa b | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Itan naa dara pupo. . . . Mo nife eré itage naa, ifokansona ati bi won se gbe awon asa at ise Naijiria jade. O dara, o si lo geerége. Genevieve Nnaji tún dára lónà tó yanilẹ́nu. Àwọn ẹjọ́ ilé ejó náà dábii tòótọ́. Mi ò mo ìdí tí alágbèéyẹ̀wọ̀ tó ṣe ti tẹ́lẹ̀ fi fún-un ní ìwòn méfa... | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
oodua heritage international organization osun state branch members oodua heritage omoluabi ni wa ooo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹni tó ńsáré tó ńwo ẹ̀hìn, ó di dandan, kó fi ẹsẹ̀ kọ. / Whoever keeps looking back while running, will certainly stumble. [Ignore distractions; stay focused and keep moving.] #Yoruba #proverb | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Fowó wónú, má fi sèbínú.👊🏿 a real life illustration. #Yoruba #OroIsiti #OroIyanju #subtitled https://t.co/uXVJ4YudZF | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
èyí ni ewé àfòmọ́ a óò sá a ní oòrùn yóò gbẹ dáadáa a óò lọ̀ ọ́ kúnná kí ẹni tí ó bá ní àrùn rọ́parọsẹ̀ ó máa fi fọ́kọ mu | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ẹkáàárọ̀ o ìyá alámàlà Ìbàdàn. ṣé ìsaasùn ọbẹ̀ ò yọnu? | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo gbàdún pé mo rí àwọn mélaǹdì àti áilàndì tí wọ́n lò, èyí yàtọ̀ sí àwọn eré mìíràn. Èkó jẹ́ ibi tí ó rẹwà láti ya fíìmù, pàápàá tí ó bá jẹ́ wípé àwọn èyàn aláràmbàrà ni wón lé lò gẹ́gẹ́ bi aṣe rí i nínú eré yìí. Àwọn apá ìjàm̀bá máa ń jẹ́ ì... | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: @user eseun gan. A ki yin fun akitiyan yin. Awa na o ni sere legbe peturolu rara. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ara ẹyìn náà la tí ń yọ epo eésan ògùṣọ́ èkùrọ̀ àti àdí dúdú bákannáà ni ewé fánrán ewé ọ̀pẹ àti ọ̀wá igi ọ̀pẹ ló bí | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Reposted from Mr Done - Reposted from @user - Èdè Yorùbá L'árinrin l'órí Rédíò Adaba88.9FM pẹ̀lú @user @user @user @user E maa gbo Tele wa 👉@user #edelman #ede #yoruba... https://t.co/UUvGqSxzsA | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ní ìgbẹ́jọ́, kò gbọdọ̀ sí ariwo, gbogbo agbègbè yó pa lọ́lọ́, kẹ́kẹ́ á pa mọ́ wọn lẹ́nu. A óò gbọ́ """"""""ká gbóhùn... #IdajoNileYoruba #Asa https://t.co/sK9Chwo12N | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#orin>~ Ẹ máa pe ko ṣẹ. Àṣẹ!2ce L'óní ọjọ́ aje. Àṣẹ! Aje a wá wa wale. Owó a wá wa wale... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òṣì lásán | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Egbe Oselu UPN ti yo apoti ni idi Oludari Dokita Frederick Fasehun! Wan ni wipe onijekuje ni Dokita Fasehun. Ogbeni Manzo ni Oludari tuntun | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ibo oôdun 2015 ti n sun moôle,Haa, Atiku fee ba ti Jonathan je o http://t.co/EprZkrfNhk | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: @user @user Mo ferun bi eshen lo ede yoruba lati so fun awon eyan nnkan ti o selee ni adugbo yin. E ku ise"""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kò fi ọ̀kan pe méjì fun. Ó mú idà Àjàṣẹ́, tí òhun fi jagun, lé Ajíbógun lọ́wọ́, láti fi tẹ̀síwájú nínú ìrìn àjò rẹ̀ titun. Ajíbógun gba Ìlà Òòrùn Ifẹ̀ lọ, pẹ̀lú idà Àjàṣẹ́ lọ́wọ́, títí ó fi wọ ilẹ̀ Iléṣà. Ajíbógun tẹ̀dó sí ìlú kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àpèmọ́nraẹni làá pe tèmídire tèmídire oooooo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìdánwò Yorùbá News Alert: 👇 Bí ó bá dá apá kan ojú ẹni yí mọ, alakoso @user yóò fi káàdì ìpè elegberun méjì náírà sórí ẹ̀rọ ìléwo rẹ. Máa tẹle @user https://t.co/MVboRziOH1 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Tóò, Yoòbá ní ẹnu onípọ̀n la ti ń gbọ́ pọ̀ọ́un, òun lẹ ti gbọ́ yẹn lẹ́nu @user nípa ọ̀rọ̀ #LASU. Nǹkan yóò ṣì dára ni wọ́n fi yé wa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
òtútù = òórùn òrùlé = òòlé ọ̀lẹ̀lẹ̀ = ọ̀ọ̀lẹ̀ = oókọ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Tí mo bá gbé ẹran mì láì f'eyín kàn án, kíni mo ṣe? #ibeere | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìtàn tó dára dé lè. . Ohun tí mo rò nípa eré yìí tẹ́lẹ̀ ko ní èyí. Ó dára ní ìlọ́po mẹwa. Ọ̀rọ̀ oríṣiríṣi tó ń kojú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní ọ̀kò kan àti bí won ti jọ ṣíṣe papọ̀ láti ṣe àtúnṣe ọ́ tayo. Mo ń dúró de sísìn kejì. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ipa kékeré kọ́ ni àlọ́, ìtàn àti ìṣẹ̀lẹ̀ àtẹ̀yìnwá nínú àṣà. Ka bí àwọn oníṣẹ́ ìwádìí kan ní Asia ṣe lo àlọ́ àti ìtàn ìbílẹ̀ fún ìpolongo ìtọ́jú àyíká. #OhunAgbaye https://t.co/bkPDirrbfT | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
happy international womens day to every girl and woman and all persons that identify as female in the world a ku odun iya iya ni wura iyebiyeojo ti iya bakuni dingi eni womi | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìtàn ìbànújé̩ tí àgbékalè̩ rẹ̩ kò dára rárá. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Eré àtìgbàdégbà. . Eré eléyì kàn ń fi ara rẹ̀ pe eré bàálù ojú òfurufú tí ó ní ìjàmbá ni jàre. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ó ṣe'ni láàánú, ọ̀pọ̀ t'ó pe ara wọn ní ọ̀mọ̀wé, gbajúmọ̀ àti ọ̀tọ̀kùlú ni ò kọ'bi ara sí ohun abínibí. #OsuItanAtehinwa | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: 23. Nítorí náà, kí àwọn ènìyàn lè máa gbọ́rọ̀, kí wọ́n sì le máa sọ̀rọ̀, @user @user @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Alákọ̀wé nbẹ́ ní ìlú #Greece báyìí! Ẹ wo Òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀ ṣe tan'ná kalẹ̀ sókè. Ọlọ́run tóbi!! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
today we bring you a famous yorùbá proverb you dont know its ending ogún ọmọdé kò le ṣeré fún ogún ọdún ṣùgbọ́n bí wọ́n bá ṣeré fún ogún ọdún àpẹẹrẹ oríburúkú ni photocredit | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òjò náà wá yàgò fún oòrùn | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àgbálùmọ́ yìí dùn bí i kà á sí nnkan. https://t.co/9UQ5gDS3bA | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ǹjẹ́ ìwọ́ fẹ́ lo orúkọ àbísọ rẹ? Ibùdó ẹ̀rọ-alátagbà mìíràn ní """"""""""""""""ìlànà orúkọ tòótọ́,"""""""""""""""" ṣùgbọ́n èyí kò rí bẹ́ẹ̀ mọ́. Bí o bá fẹ́ lo orúkọ àbísọ nígbàtí o bá ń forúkọ-sílẹ̀ lórí ẹ̀rọ-alátagbà, máà ṣe bẹ́ẹ̀. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ibi (place) + ìba (to lurk) = bùbá [ìpọ̀nrí ajá ò gbọdọ̀ bá ẹkùn ní bùbá - the dog dare not meet the leopard in its hideout] #InYoruba #Owe | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ̀ranko wo ni à ń pè ní esé? 1. Ológìnní 2. Eku 3. Ajá. #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#atunko """"""""Ẹyẹ àdàbà! Ẹyẹ àdàbà! Ẹyẹ àdàbà tí ńfò lókè lókèe, wá bà lé mi o. Ojúmọ́ ti mọ́, mo rí ire o..."""""""" O ṣeun @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ọmọ ilé... Ọmọ agbo ilé... | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Irú alágbéká wo lẹ nlò? iPhone fúni lánfàní àti f'àmì sọ́rọ̀. Nípasẹ̀ ilé iṣẹ́ asọ̀rọ̀mágbèsì ti Abẹ́òkúta tó pèsè rẹ̀ fúnwa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Gbogbo ẹni tó bá pa'gúnugún kìí ká'gún. Gbogbo èèyàn tó bá p'àkàlàmàgbò kìí p'óṣù. Ikú òjijì fún gbogbo àwọn tó fẹ́ máa… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Celebrate Iya ní wurà, #AdeyemiMichael #yoruba #9ja bidow2509 ibitoyeyetundea mikalia.ibitoye denerouno1 @user, keep bossing it ❤ https://t.co/Ycj0IlXO4h | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
4.Èwo nínú àwọn ọba wọ̀nyí ló kọ ìwé síjọba Gẹ̀ẹ́sì ní 15/10/1881? A. Ọba Adéyẹmí B. Ọba Síjúwadé D. Ọba Ẹṣìnlókùn #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bìríbìrí l'ayé ń yí, ẹnìkan 'ò sì lè lo'lé ayé gbó @user #idanoripapa #Brasil | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ewée tàgíìrì ni àwọn Yoòbá, ma ń gbo fún alábiamọ tí kò sí omi lọ́yàn an rẹ̀ mu, kíá ni omi á dé ọmúu rẹ̀. #Tagiiri #Ewe #Eso #Egbo #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Láti tẹ̀síwájú nínú ìgbélárugẹ èdè abínibí, à ń wá àwọn tí èdè Yorùbá jẹ lógún, tí ó nífẹ̀ẹ́ sí ìdàgbàsókèe tiwa n tiwa láti… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ta ló máa gbà wá lọ́wọ́ àwọn ìjọba òde òní? Àwọn oníṣẹ́ ọpọlọ ni wọ́n ń fi ìyà jẹ. Bí wọn kò t'akọ̀ròyìn mọ́lé, wọ́n á pa… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Àjàpá ní kò sí oun t'ó dà bí oun tí a mọ̀ ọ́ṣe; ó ní bí òún bá ju ẹyìn sẹ́nu, òun a tu èkùrọ́ sílẹ̀. #EsinOro🐎 #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èwo nínú oúnjẹ wọ̀nyí ni a fi àgbàdo ṣe. 1. Ọ̀jọ̀jọ̀ 2. Ègbo 3. Kàsádà #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìwà rere lẹ̀ṣọ́ ènìà | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ajẹ́pé n ó kọ nípa rẹ̀ ní | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ilu Eko la fi ikale ajinde odun yii si oya e je ka lo *ijo* | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ẹ̀rọ̀ pẹ̀sẹ̀ n tìgbín. #AlayeOro #EsinOro #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
imudogba akọ ati abo | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Báyìí ni Tatalọ ṣe jẹyo nínú orúkọ Tatalo Alamu, àgbà olórin ìlú Ìbàdàn https://t.co/lBmeCKezxx #TataloAlamu #bbcnewsYoruba #Sekere #OrinAgba #TiwanTiwatv #Yoruba #YorubaCulture #YorubaWriter #AfricanMusic #MusicJournalist #Music #Yoruba #OlayemiOniroyin #BBNaija | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ona lo jin, eru ni baba. #proverbs #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Jiji ti a ji looni, a ji s'owo, a ji s'omo, aiku baale ooro! Eku ojumo.""""""""@user: Ẹ ẹ̀ jíire bí? ẹ̀yin ọmọ Oòdu ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ká ṣọ́ra rọra mu omi inú ọ̀rá ike ká má ba kó aàrùn onígbáméjì | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹní bá lè kọrin ìfẹ́ẹ yorùbá yóò gbẹ̀bùn owó ìpè o sì lè kọ sí olùfẹ́ ẹ ní yorùbá kí o yàá ní fótò kò fi ránṣẹ́ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìrújú = confusion. Rújú = confused. (Ọ̀ràn náà rú mi lójú - the matter confused me) #InYoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
o ye bee yo je ari ko gbon fun awon yo ku | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
bó lé lógún ọdún táa ti fi adẹ́mun jọba kò ní yé ọrùn ọ̀pẹ ẹ́ wò even after years of being crowned a king the | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Alaanu ni oluwa, ka anu re jumo wa wari. Amin ase! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Epo ni a fi ń dín àkàrà elépo; kengbe, a sì le fi dín nǹkan mìíràn. #Epopupa #Yoruba #Food #Ounje #Akara | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user - Ó da o ọmọ Yoòbá tòótọ́, máa ṣe àtúnṣe | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
já ra rẹ gbà lọ́wọ́ ọ àwòrán tóún rí ni lára yìí | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ìtàn tó lágbára . . . . Eré yìí ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀kọ́ nínú. Zainab Balogun túmò ipa náà dáadáa. Tí o bá ti sọnù, ǹkan tí o nílò ni eré yìí, yóò sì tọ́ ẹ sónà padà sí ìlànà ọlọ́run. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
alákágbá = àjànàkú = awun = | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Oluwa a dowo irk e duro fuwa o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
wúrà gold golden precious | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ yára tẹ̀lé @user láti gbádùn àwọn àwòrán Ìlú Ṣakí ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. #ThinkOyoRoadTrip #Saki | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ kú ilé o. http://t.co/ekubk0rf2S | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọranyan àti imunilara! Àwọn àwọ̀ tó rẹwà àti imura tó lágbára. Igun àwòrán pé o sí abala kọ̀ọ̀kan títí di ìparí. Ó kuomoose fún yíyà àkọ́kọ́! | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: @user Kini ipinle oruko #Yoruba ganngan? Gege bi oruko | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Omo to so wipe Baba oun se obe ko dun, itan bi won se le iya e lo lo fee gbo #tweetYoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èsìn ò pé k'á má ṣe bí ẹ̀dá ẹlẹ́ran ara, a ò lè dàbí Ọlọ́run ẹ̀mí mímọ́, a kàn ń gbìyànjú ni. #YorùbáRonu | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user ẹ kú ojúmọmọ o! Mo tọrọ gáfárà, ẹ dákun ẹ ṣe àtúnṣe sí ọ̀rọ̀ yìí. Oòduà á gbè wá o! #TweetYoruba https://t… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.