text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
.@user kini gbo gbo serenren yi, ema lo si ile ki elo ma je eba ko lobe. @user ma pe yin ti o ba kan yin. https://t.co/S4YQpXCp6Y
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo fẹ́ràn rẹ̀. . . . Fíìmù yìí ga jù. Ìtàn ere náà gbayì bẹ́ẹ̀ sì ni . . ère ṣíṣe rẹ̀ kò bàjẹ́
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Eré Naijiria to dára jùlọ. . Lionheart ṣiṣẹ̀ bi eré oniṣe àti àwàdà láì gbìyànjú. Àwàdà n ṣàn ó sì fi àsà àti ìṣe Naijiria hàn ni ọ̀nà tí ó lẹ́wà.. . Àwòrán naa si dara. . Kú iṣẹ́ Genevieve Nnaji, o sé ti oò dójú ti wa.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Alakikanju, ọlọ́pọlọ pípé àti olódodo ọ̀dọ́mọdé ni Yẹmí jẹ́ nínú ìtàn àròsọ yìí tí Kọ́lá Àkínlàdé kọ. Kíni ojú rẹ̀ rí nípa ìsọdodo àti ìwà òtítọ́ tí ó ń hù? Kíni ìgbẹ̀yìn Yẹmí? Ǹjẹ́ òdodo gbèé? #YemiDaBira #Atelewo #Yoruba #YorubaBooks https://t.co/JDyz4xw89f
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user Nkan dara dara ni eyi je #tweetinyorubaday
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ikú tó pa aládìẹ...
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Amin""""""""@user: Ọjọ́ Ẹtì, ọjọ́ kejìlá oṣù ìgbé. Kẹ̀rẹ̀kẹ̀rẹ̀ oṣù kẹrin ọdún ńlọ. Èdùmàrè dákun-dábọ̀ ṣọ́ wa ja'lẹ̀ ọdún ...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ÀFIN ÌṢẸ̀M̀BÁYÉ ÀKÚRẸ́ Ní àsìkò 1150 ni wọ́n kọ́ àfin náà. Ọba mẹ́ta dín l'áàdọ́ta (47) ni ó ti gun orí ìtẹ́ nínú àfin yìí, láti orí ọba àkọ́kọ́, ọba Ọ̀mọrẹ̀mílẹ́kún Aṣọdẹbóyèdé. Wọ́n ṣì ń lo àfin náà, fún àwọn ètùtù oríṣi kan. Àwòrán: Tribune online https://t.co/YajhhkoaxB
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#Repost from bbcnewsyoruba with @user.app ... """"""""Kí ni kí n ṣe o?"""""""" 🤔 Ẹ fún ọ̀dọ́mọkùnrin yìí classy_jesters ní àmọ̀ràn! 😅 #BBCNewsYoruba #Yoruba #comedy #skit #comedyskit @user Ajegunle, Lagos, Nigeria https://t.co/9VsyGgrFxU
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Tṣọlá àt'àbúrò rẹ̀ t'óyè náà tọ́ sí ò le è di ọba nítorí àṣà ìlú ni, ọmọ ọba tí ìyáa rẹ̀ kì í ṣ'ọmọ #Itsekiri tàbí #Ibini ò le è jọba.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#Nigbatiwonlo, ìmọtara ẹni nìkan, ìwá àwòdì jẹun èpè sanra gba ayé kan. #BHM
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ kú Ọjọ́ ọ̀sẹ̀ o.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ẹní bá dúpẹ́ oore àná yóò rí òmíràn gbà. / Whoever gives thanks for yesterday's kindness, will receive another. [Attit…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
idamewa kii se dandan pasitọ tunde bakare ijọ ti alufa ba n sanra ti awọn ọmọ ijo si n ru olorun ni yoo dajọ afeyin pẹran o e wo ekunrẹrẹ fidio yi nibi
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wọ́n ti jí gbogbo àlá ọ̀laa wa. Pàdé @user àti àwọn ọ̀dọ́ mìíràn lọ́la ní #CMS bẹ̀rẹ̀ láago mesàn án àárọ̀. #Nigeria #StolenDreams
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
òwú kì í là kí inú ó bí olóko àwa ó là bẹẹrẹ bí ọba eréke bí ọjọ́ bá là gbogbo igi oko ni yóò máa dán gbinrin ǹjẹ́ àwa yóò máa dán gbinrin ìyẹn bí aáyán inú ṣálángá àwọ̀ wa kò ní bàjẹ́ lọ́lá ọlọ́run ire ni tiwa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àjàkálè àrùn tó ṣì tún le ṣẹlẹ̀. . . . Ó jẹ́ eré tó tayọ, tó ṣì jẹ́ yọ pẹ̀lú ohun tó ń ṣẹlẹ̀ ni àyíká wa. Ó dára ju gbogbo àwọn eré tí mo ní lọ́kàn lọ. Eré na ṣàfihàn ohun tó pọ̀. Ó jẹ́ àjàkálè àrùn tó lágbára àkókó ni ìwàláàyè mi. Má nì fẹ́ láti ra kásẹ̀tì rẹ̀ ṣọ́wọ́, mo tí wá káàkiri US ṣùgbọ́n mí ó tí ríi. Ṣé amo b...
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: @user A ku ojumo ire. Ire gbogbo ni o ma je ti wa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user @user @user @user Lóòótọ́ iṣẹ́ ti ṣe nípa #TweetYoruba Bóyá ká dojú ìjà …
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: pari owe yi: Bi a bá ní kí ará ilé ẹni ma l’owo,..@user @user @user @user @user ...
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ṣebí láyé awólọ́wọ̀ bí ìwé tí o kà ni búrẹ́dì rẹ yóò ṣe tóbi tó a gbéwèé sórí tán a bẹ̀rẹ̀ sí ní fi ẹsẹ̀ fọ́n ìgboro kiri
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#iroyin, #yoruba, Awon akekojade Ilesa Grammar School wo Gomina Aregbesola lo sile ejo… https://t.co/3PGXjuO5MY
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àdélébáre ni ètò tí a gbé kalẹ̀ fún àwọn arìnnà ti ó ń lo sílé láti ibi iṣẹ́ òòjọ́ọ wọn. Agogo mẹ́rin àbọ̀ ní àárín ọ̀sẹ̀ (Ọjọ́ Ajé sí ọjọ́ Ẹtì). A ò ní rìn lọ́jọ́ tí ebí bá ń pa ọ̀nà. Àdélébáre, arìnnà kore, àfòyàibi!!! #Yoruba #Bond929fm https://t.co/HGTG3hDoy1
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìsekúse gbàá! Àwọn ẹni yìí kò ní nkán ṣe. Dákun, má fí náírà rẹ fún wọn lérè.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ogaaaa kilo waade tiwon o kede ijoba wa tuntun na rii abiii erun nbawon nii
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ódàbí eti bu omi ìfé arewà yìí mu ojúù mi jẹ adùnun adú ọmọ tó rẹwà bíi ọ̀kín lálẹ́ yìí mo ti yó wàláhì ọmọ n
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user ahaha... Tani n je omo Akówápá niwaju omo akú yányán na... àìmèrò ni imu kiniun pe ajá ni ègbón oun!... ...
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo kórira bí wọ́n ṣe fún eré yí ní àkọlé.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user A jẹ́ pé òwe àgbà ni. Àgbà òní tán nílùú o! Ìmọ̀ náà ò ní jọ́bà.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user ase eledumare...ipade ayo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ǹjẹ́ẹ̀wọ́ mọ̀ pé Ẹ̀gbá pín sí ìṣọ̀rí-ìsọ̀rí? Apá kan ni Ẹ̀gbá-Owódé; Ẹ̀gbá-Imọ́; Ẹ̀gbá-Ìgbèìn; Ẹ̀gbá-Ìgbórè. 1842 l'Ẹ̀gbáa Sàró dé. #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn àmi bi ẹ̀fọrí, araríro, òtútù, rírẹni àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. #malaria #WorldMalariaDay #yoruba #RollBackMalaria
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: ṣàì jèrè tèmi Igba ni ewé olújèrè Alárá ṣe tirẹ̀ Ó jèrè ayé Igba ni ewé olújèrè Èmi kà ṣàì jèrè tèmi Igba ni ewé ol…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Báwo wá ni orúkọ Ìjẹ̀bú-Òde ti jẹ́? #Irinajo #Ijebu
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gbòógì orin ìbílẹ̀ ni Ṣákárà, ǹjẹ́ o mọ olórin Sákárà kankan? #Orin #Sakara #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ ti gbìyànjú ẹ tún bọ̀ ṣe díẹ̀ si kí ẹ fi parí rẹ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gbogbo ìyàwó tó fẹ́ pátá ni ọmọ tí wọ́n bí ń kú. Babaláwo ni bàbá tó bí mi, aláwo ni màmáà mi náà, olórìṣà ni wọ́n. Ìgbà táwọn ọmọ wọ́n ń kú ni wọ́n lọ darapọ̀ mọ́ ìjọ Sẹ̀lẹ́, Sẹ̀lẹ́ ni wọ́n ti wáá bí èmi àtàwọn yòókù mi tí a ṣì wà títí dàsìkò yìí...
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
K’Ọ́lọ́run gbàwá lọ́wọ́ iṣẹ́ bóojí o jími. Kó fiwá lọ́kàn balẹ̀. K'ọ́nà àtijẹ wa ó má ṣòro. 🙏
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo kí gbogbo onígbàgbọ́ ọmọ-lẹ́hìn Kristi. Ẹ kú orí ire ti àjínde olùgbàlà o. Iyè àìnípẹ̀kun ọ̀hún kò ní ṣàìjẹ́ tiyín o!! #ajinde #Jesu
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Láwòlé sùn, gbogbo ọ̀táa ìlú mi yó d'ọ̀tá ayé. Ayé tó ṣe ilá tí ilá fi kó yó ṣe wọ́n po lọ̀kànkan èjèèjì. Àṣẹ́ gùn ún. #Osetura gbé e lọ.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Happy #MotherLanguageDay to you all. A ku ajodun, eyin omo #yoruba https://t.co/1MF10cxx0y
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹgbẹgbẹ̀rún ọ̀nà ni wọ́n fi pa òtítọ́ run kó ba mú wa ṣe bí ṣe ń ṣe
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
yoruba loni ijo bẹ́ẹ̀ ni o àwa la ni ijó
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ko sẹ́ni ti ò ní ku.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user adura ni kaa gba pe ki olorun eledumare ki o ko won yoo, ki o si ma fi iru se ile Naija.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Oro Akpabio yi ma dun yin lopolopo o! Sebi beyin na se gbe gba oti, ti emu ijo jo, beresi polongo lori Twitter nigba ti awon omo egbe oselu APC darapo mo egbe PDP ni yen. https://t.co/D3sjqr1JWw
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Awa niyen o anikun owo omo ati alaafia ni yoo je fun wa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ní báyìí ọ̀rọ̀ mìíràn ni wọ́n wá bá wa sọ ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn sì ni
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Irorun ni gbogbo adawole wa l'oni, aase.""""""""@user: Ẹ nlẹ́ o. Ẹ kú àsùnjí. Ọjọ́ ó mú're wá o""""""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ṣé ọjọ́ orí ṣe pàtàkì nínú ètò ìlú ṣíṣe
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: ... ẹ óò ríi pé #mission; iṣẹ́ à ti gba àṣà lọ́wọ́ọ wa ni. @user @user @user @user
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn ọmọ wọ̀nyí sun ẹkùn, wọ́n ké sí ìyá wọn lọ́rùn pé kí èyun ùn pèsè omi fún àwọn. Ara Yewa ò gbà á. #ItanOdoIyewa #IyaRere #AyajoOjoIya
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
a ti bo sori ayoka araoto extra pelu ninu gidi runz show aja lo leru lati owo oladejo okediji ni oruko iwe ti a o maa ka bayii e maa ba wa kalo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user dansaki re Olorun oba..modupe temi
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ọyọ́ Aláàfin òjò pa ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ ọmọ Àtìbà. Ẹ̀sọ̀ pẹ̀lẹ́ o.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ kú ojúmọ́ o ṣé dáadáa la jí o ṣé oníkejì yín ò hanrun jù
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
tó jẹ́ pé nínú àwẹ̀ wọ́n tún lọ kọlu mọ́sálásí wọn kò mọ pé ọlọ́run tí wọ́n npè kò faramọ́ nka tí wọ́n nṣe ni
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bàtà fún ìfẹ̀hónúhàn #EndSars àti #EndSWAT. Ẹ kàn sí @user lórí +234 803 512 4311 kí ẹ ra tiyín. Ẹ sọ̀rọ̀ sókè! #EndNASSpay https://t.co/lmmGOpv9KZ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí ló ń fà! 👇Yorùbá kọ́ lèyí o. https://t.co/R2bO4y1KyA
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Njẹ́ mo gbóríyìn fún Elédùà. Olódùmarè Ọba alágbára jùlọ. Ká bií ò sí.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọdún méjì kò lónìí ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kejìlá tí balẹ̀ bí àdàbà sórí ayélujára ọpẹ́ kànkà lọ́wọ́ elédùmarè ọbaafúnniṣe
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ṣé ẹ ti dáwó? Ọjọ́ mẹ́tàdínlógójì péré ló kù o. Kí eku ilé gbọ́ ko lọ sọ fún t'oko. Kí àdán gbọ́ kí o lọ rò f'óòbẹ̀! https://t.co/0zoOWaRuY3
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìtàn àtẹnudẹ́nu rò wípé, ẹ̀sìn ìmàle ló bí àṣà orin Sákárà, Bídàá ní ìlú Núpé sì ni ó ti ṣẹ̀ wá. #Sakara #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
owó epo léwó owó ọkọ̀ léwó
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èwo ńnú #orisa wọ̀nyí ni Àjàlá alámọ̀ ire; #Sango, #Ogun, #Obatala? #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìdaomi owu ó wà ní owa onire ní ìjọba ìbílẹ̀ ìfẹ́lódùn ìpínlẹ̀ kwara òhun ni wọ́n rí gẹ́gẹ́ bíi ìdaomi tí ó ga jù ní ìwọ̀oòrùn afíríkà wọ́n tún ń pè é ní àrà inú aginjù òkè ńlá ni ó yi ká tí afẹ́rẹ́ rẹ̀ síì dùn ń wò àgbègbè ìdaomi náà tutù minimini
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Awuyewuye àwọn èdè tó fẹ́ parẹ́ yìí mà ń ta mi lára kẹ̀ẹ. #YorubaONiParun
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Olódùmarè dákun dóòlà ọ̀gbẹ́ni tí mọ́tò gbá lálẹ́ àná níyànà àti wọ Aswani...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mo sadi o apata ayeraye mo wólẹ̀ fún ọlọ́run ọba mo foríbalẹ̀ fún olódùmarè ọba ògo ọ̀gbàgbà tí í gbani
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí ni èdè abínibí? Ipa kíni ó ń kó nínú ìdàgbàsókè àwùjọ? #MotherLanguageDay #Yoruba https://t.co/dFF66k398K
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọlọ́run a fún wọn ṣe ó tiẹ̀ ti fún wọn ṣe ná
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ̀dá kàn ntiraka ni, a ò lè kọ́lé kó ga títí kó dókè ọ̀run. http://t.co/Hz0b4dzt
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èmi gẹ́gẹ́ bí ẹnìkan kì í fẹ́ lọ sí ilé ìwòsàn ìjọba, orí àwọn òṣìṣẹ́ tó wà níbẹ̀ ti burú, kòkòrò ń bẹ lóríi wọn, bí wọ́n ṣe máa ń dá àwọn aláìsàn lóhùn kò dára rárá àti rárá. Àìmọye ẹ̀mí tí ó ti bọ́ látàrí àìbìkítà àwọn oníṣègùn òyìnbó ilé ìwòsàn ìjọba.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó ku ọjọ́ Méje! Fi iṣẹ́ rẹ ránṣẹ́ sí wa. You can be the next #LawuyiOgunniran 😀 Wo https://t.co/tQJihRMGO1 fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé. #AtelewoPrize #Yoruba #Atelewo https://t.co/Lo6kHQSJbH
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gómìnà ìpínlẹ̀ Bauchi tẹ́lẹ̀ rí, Isa Yuguda wípé àwon òní ìwé ìròyìn náà lọ́wọ́ nínu wàhálà tó ńṣẹlẹ̀ láàrín àwọn àgbẹ̀ àti oní màálù l'órílẹ̀ èdè Nàìjíríà #EdeYorubaDunLeti #tuesdaymotivations #tuesdayvibe #Yoruba https://t.co/eFdNxZBHet
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ibi dan na RT @user: Kíni njẹ́ ààrò? #ibeere
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ekaaro gbogbo omo kaaro ojire. Agbajo owo lafin soya...... #TweetinYoruba @user @user
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
laipe laijino idajo yio de fun egbe oloro isis ati egbe apanimayoda bokoharamu olori amerika lo so be fun egbe aigbaye un
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Oniregbe, olojukokoro""""""""@user: Lára ìṣekúṣe lati mú oníṣekúṣe, ẹlẹ́yà ni a ti rí ẹlẹ́lẹ́yà. Ọ̀rọ̀ wo la yọ láti ara ìr…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user: @user @user ki lo n shele ni ibe oo.e gbe si wa leti"""""""" Ó jọ pé àwọn àwáwà (ọmọ-ìta) fẹ́ gbàjọba lọ́wọ́ ara wọn
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eré tí ajá fi ogún ọdún sá
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó kún fún àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ aláìlọ́pọlọ, òsì, ọ̀rọ̀ rírùn,àti eré ṣíṣe tí kò dára tó.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
aláìjẹ̀bi ló ń kú
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bí oṣù èrèlé ṣe kó ẹrù sọ́kọ̀ lọ tí oṣù tuntun ẹrẹ́nà sì lalẹ̀ bí i òṣùmàrè ni òfo ayé mi kẹ́rù sọ́kọ̀ lọ tí gbogbo ire ayé mi yóò sì bú yọ bí i ìtànṣán oòrùn ọjọ́ àti bí òṣùpá ọjọ́ kẹrìnlá ire gbogbo tí ó ń bẹ ní dúníyán kò jẹ́ tèmi títí láé
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó jẹ́ déédéé pẹ̀lú ìbànújẹ́, ó dààmú ọkàn ṣùgbọ́n ó ní ìkópa tó yani lẹ́nu.. . . . Mo dàgbà ní àsìkò yìí àti ní ìbànújẹ́ pẹ̀lú díẹ̀ nínú àwọn ọ̀ràn tí a gbé jáde nínú fíìmù yìí. Mo ní ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ tí ó ní ìrírí “ọ̀gbìn” àti pé àwọn àbájáde rẹ̀ wà nínú ìgbésí ayé rẹ̀ àti ẹbí rẹ̀ lónìí. Fíìmù náà jẹ́ ìbànújẹ́, ṣùg...
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ti a wà kódà ni Kansu tí so pé kí àwọn ọdọ máa kopa títi di asiko yii, wípé komisona ni ó, gómìnà ni, ọdọ náà ni, tí ẹ bá wo irin àjò wá láti ìgbà yẹn sì asiko yii, o ju irẹ ni a fi ṣe mí ó fi ona kankan tán yín rárá. - @user
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
📣 New Podcast! """"""""Asa ati Orisa ile Yoruba 4"""""""" on @user #culture #yoruba https://t.co/zuPjDYnDBM
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ayẹyẹ ìrántí ìgbà tí Olódùmarè dá ilé ayé àti ohun gbogbo tí ń bẹ lórí ilẹ̀-ayé ni Ọlọ́jọ́ jẹ́. #IleIfe #Yoruba #Olojo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ọba ògo ṣeun ṣeun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kàbàkàbà = roughly (èrò-ọjà sáré kàbàkàbà nígbà tí wọ́n gbọ́ he - market people ran roughly at the sound of an uproar) #InYoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kò ṣeé ròyìn fún àwọn tí ó ní ìmò
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ẹ̀yin ọmọ lẹ́hìn krístì ṣé ìjọsìn dùn kí lààfáà wí ṣé pé kí a máa ní ìfẹ́ ọmọnìkejì bí arawa àbí àti pé ìfẹ́ ọlọ́run ló ṣe pàtàkì
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user fẹ́rẹ́ = kí ó dínkù, fẹ́ẹ́rẹ̀ = ó kù díẹ̀, fẹ̀ẹ̀rẹ̀ = ní ìdájí, kílẹ̀ t'ó mọ́. #Idahun #Ibeere
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#OroAmoye Oye to kan ara Iwo yoo kuku kan ara Ede. Ohun gbogbo ti eda ba n se laye ko fi suuru si nitori suuru ni baba iwa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Aworan: @user se ipade pelu awon olori ati atokun igbimo asofin @user @user http://t.co/sVOsiOKuBK
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
10. Orúkọ-àmútọ̀runwá wo ni à ń pe ọmọ tuntun tí ó fi àwọ̀n bo ojú/orí? A) Ato B) Òjó D) Àìná #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
òpin ọ̀sẹ̀ o mà káàbọ̀ o máa wolẹ̀ máa rọra
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nínú eré wo ni fọ́nrán yìí wà. #TundeKelani #Yoruba #Nàìjíríà #Ibile #Saworoide #ÈdèYorùbárẹwà https://t.co/JUHDfkyml2
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
lónìí ọjọ́ ìṣẹ́gun olúwa yó bá wa ṣẹ́ gbogbo ogun ayé wa kò ní ṣẹ́ kan kù a ó lọre a ó bọ̀ ire ọ̀nà ò ní nà wá
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
...ó ku ọjọ́ kan sọ́jọ́ ìsọmọlórúkọ, ọwọ́ Èkúté dẹ ẹran ìgalà ńlá, nigba ti ologbo gbo pe oree re pa ìgalà, inú rẹ̀ dun #itan #oremeji
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train