text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
RT @user: """"""""""""""""Mi ò lè wá kú"""""""""""""""" kan kò lè j'oyè ilé baba rẹ. #EndSARS #sorosoke | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Tó omo re, kí ó lè fún e ní ìsinmi, kí àwon ará ìlú náà lè wà n'ìsinmi (Train ur child so you & d community can have peace). #TweetinYoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user Oruko temi ni Olufunmilayo Amoke. A bi mi si Ketu. ÖMÖ isale eko ni mi. Eko, a r'omi sa legbe legbe #TweetinYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
píníṣínkékeré youngtender láti píníṣín lọmọ náà ti já fáfá the child became smart from tender age | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
alàgbá lọ ọdúnun ni mo kọ́kọ́ fi ojúù mi kòró kan àjàpá inú ààfin ṣọ̀ún ògbómọ̀ṣọ́ yìí níbi tí ìjàpá yìí gbó dé bí wọ́n ń bá ń ṣe ìwúre wọ́n máa ń fi ọjọ́ orí ẹranko yìí wúre wọ́n á ní wà á pẹ́ láyé bí ìjàpá ààfin ògbómọ̀ṣọ́ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
afọbajẹ rí í wípé ó yẹ kí a gbóríhìn fún irú ẹni bẹ́ẹ̀ tó wò ṣùṣù bọ́bakú ni abọ́bakú di oyè | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ebi npa olódodo. 😢 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Oruko mi ni Oyeyinka Esther Adebisi Abi mi ni ilu Eko sugbon omo Ibadan ni'le oluyole nimi #TweetinYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Olohun maa fi ikan gbakan lowomi🙏 #Yoruba https://t.co/JexSkvt7Pn | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user Ọlọ́run á ṣe èyí tó dára. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Mo gbádun àbá òjògbón @user yi! Lati òní lo, Arinletikun ni a o maa pe 'penguin' ni Yooba o! @user @user… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
pósí òkú àgàgú rèé lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ẹ gbankogbì tó dá làásìgbo àárọ̀ sílẹ̀ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ohùn tí wọ́n fi mọ́ àwòrán tí wọ́n ń pín kiri tí òpùrọ́ náà pe orúkọ ara rẹ̀ ní bàsírá tí ó tún ń búra èké wípé obìrin apenipa náà pe òun kì í ṣe ojúlówó irọ́ baba irọ́ ni | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
O ye awon adulawo to wa ni oke okun daradara. O so nipa iririi mi gege bi adulawo ti ko gbe nile adulawo ti o si n gbiyanju lati wa ibugbe miiran. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
ìkáwọ làbà ni àpò agbára ọba tó wà lórí ìtẹ́ wà làbà ni a tún ń pè ní ẹ̀yọ̀ ọba ẹ̀yọ̀ oníko ni ọlọ́pàá ẹ̀yọ̀ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Oba Ajoke aye, Oba Asake orun #Yoruba https://t.co/T1ji2BrLJQ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user, Kini o ma sele si awon omo ologun atun'ra eni da ti Aare @user so pe ohun ko'fe ni ise ologun Amerika 🇺🇸? #TweetInYoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹdan ni ọ̀pá ni àwọn àgbà fi ní ẹdan kì í kú kì í rùn ojú ẹdan kì í fọ́ ní ilédì | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn ohun towuni lati wo ṣùgbọ́n gbogbo ìṣètò erena ko dára | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
13. Pa òwe méjì tí ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú 'ẹni'. Fún àpẹẹrẹ, ẹni gbókùú àparò gbé aápọn. #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
A kì í wo ìyẹ́ adìyẹ nílẹ̀, kí a wá fi ìrù àkèekèé rin etí. @user @user #Yoruba #Opaisokan #YorubaUnity | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Àwọn Yorùbá ní, """"""""k'á gbóyè f'ólóyè, k'á gbádé fún ẹni t'ó ladé"""""""", èyí ló mú kí Àjọ Ìṣọ̀kan Àgbáyé tó ń rí s'Étò Ẹ̀kọ́, Ìmọ̀ Ìj… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀yẹ́ là peregede. Ojúmọ́ tuntún mọ́. Ẹ kú ojúmọ́, ẹ kú ojúmọ̀, ẹ kú ojúmọmọ gbogbo alààyè. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
amin o mo dupe e ku igbadun ilu wa yii o emi naa ti n tele yin o a ko ni tele ara wa wo inu iparun o e kaaro | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọpẹ fún Olúwa o! Mo bá àwọn òbí wọn yọ! Ìjọba gbọ dó ṣiṣẹ láti dákun ìwà òdaran buruku yi láwùjọ wa. #TweetinYoruba https://t.co/FR9KKat7bw | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àìfọwósí | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
owó ìṣákọ́lè oko tún gbómi ọkà ìjà kaná ní títí di | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user rara o. MCFC yato si MUFC. E tun eyi ko. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Níbo wá lorúkọ #Nigeria ti wá? #IndependenceDayBroadcast #Yoruba #yobamoodua | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
mo ń gbọ́ ìró àrá omi òjò náà kán lé mi lórí ẹ jẹ́ n yáa gbọ̀nà ilé mi lọ kí òjò tó ká mi mọ́n ìyókù dọ̀la | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ayewa lase Edumare""""""""""""""""@user: Mo júbà o. Gbogbo ọmọ káàárọ̀oòjíire. Ẹ jẹ́ kó yẹ mí o. #mojuba #yoruba"""""""""""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
omo yoba post ọmọ ooduà on afroterminal | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
iná mú ọjà epo ní dálékọ́ muṣin láàárọ̀ yìí | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ibi tó ń bẹ níwájú ẹ yẹ̀ba, ajogun tó ń bẹ lẹ́yìn ẹ bìlà! Àkówábá, àdáwábá kò ní jẹ́ ìpín-in wa láṣẹ Elédùmarè. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
òbí rere ni ìwọ tí o bá mọ rírì ọmọ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìdí abájọ rèé pé ò báà pa ẹgbẹẹgẹ̀rún èyàn ìjọba ò báà kó irinwó ọ̀kẹ́ owó jẹ ọpẹ́ ni fólóldùmarè òní lá ri kòsẹ́nií mọ̀la | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
adupe o awon amujuto ni wipe ka dupe ile ise yin ko ni jono o eyin na e ma fi peturolu sere legbe ile ise | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
9. Iyọ̀ tàbí __, orí tàbí ___, esè tàbí ológìnní, àáké tàbí ẹdùn. #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Toò. Wọ́n ní ìlú kan tún ń bẹ lábẹ́lẹ̀, àti lábẹ́ odò yìí. Ìyẹn tún di ọ̀la ọjọ ire. Oùnjẹ ni ọpọ́n sún kàn wàyí. #Ronda #Andalucía #Spain | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
4) What is the name of the deity that stands as the connection between the living and the dead in Yorùbá land? 4) Kíni orúkọ Òrìṣà tí ó dúró gẹ́gẹ́ bíi àmì láàárín àwọn aláyè èèyàn àti òkú wọn? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kòjẹ̀gbin; kò-jẹ-ẹ̀gbin ni à ń pè é torí ibi àtẹ́lẹsẹ̀ yìí kìí sábàá dọ̀tí bíi àtẹ́lẹ́-ẹsẹ̀ gan an fún 'ra rẹ̀. #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ láti alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ dé girama fún ọmọ #Naija. Ìgbésẹ̀ rere ni bí ẹ bá lè ṣe é. #NGConfab | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
abayomi pa orebinrin re londo n nileejo ba ni ki won yegi fun un | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
the english call it lake yorùbá á ma pè é ní odò adágún | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
igbagbo temi naa niyenmo gbagbo pe apa eledumare ka gbogbo re | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
oye mi oo°˚˚˚° gt gt tá ló yé ise dale awa omo yorubakare | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Kaaro ajibi. Se alafia ni gbogbo duniyan wa. Aya nko, omo nko?""""""""@user: A jẹ́ pé Ọlọ́run Ọba ni ọpẹ́ yẹ lójúmọ́ àti lój ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Kò sí ohun tó ní ìbẹ̀rẹ̀ tí kò ní lópin. / There is nothing that has a beginning that won't have an ending. [Keep hope… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ká dúpẹ́ lọ́wọ́ ọrùn tó gbé orí dúró; ọ̀pọ̀ ẹran ló sún mọ́ orí tí ò ṣe nǹkankan. / Wẹ ought to be thankful to the nec… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user @user @user @user Charles Luwanga, Kizito ati be be lo. Won a fe to ogbon. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ojúmó ire o. A sì ku oṣù tuntun. Òní á san wá o, àmó e má gbàgbé wípé Ọjọ́ kan ni t'olè, Ojó kan ni t'Olóhun https://t.co/… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user @user @user @user @user @user @user @user @user Diezani o ni ku, ko ni run, sugbon ko ni won nle dokita nigba Kan kan... Iye ti Diezani ji ko emi o mon o sugbon koni dafun #TweetInYoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Queen Salawa Abeni for the night! """"""""Sebi l'ọfe l'ọfe ni Baba fun wa Sebi l'ọfe l'ọfe ni Baba fun wa o Iṣẹ́ Olúwa, àwòyanu ni Ọlọ́run o gbowó o, ko de gbobì o Kò gba nkankan kó tó fún wa látẹ́gùn o Sebi l'ọfe l'ọfe ni Baba fun wa o"""""""" 🎶🍷#OldHeadMusic #Classic #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kò sẹ́ni mọ Òkòló nílùú Ọ̀yọ́-Ilé, ààfin nìkan la ti mọ̀ ọ́ gẹ́gẹ́ bí apako fún ẹṣin ọba jẹ. Bíkòṣe nínú aàfin, ta ló tún mÒkòló! #ItanDowe | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré ńlá. Bí ó tilẹ̀ jẹ̀ wí pé òun kọ́ ni Fíìmù tí ó dára jù rí, ṣùgbọ́n ó dára ju ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù Hollywood lọ.. . Àlà àti ìlànà ilẹ̀ dúró régérégé, àwọn àwọ̀ wọ ni lójú pẹ̀lú ẹwà wọn, ìtàn náà ò ṣàìdára. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: @user @user iro nparo fun iro Tami afoju tan dolphin sun ,johns tiosun talk to. Oponu agbalagba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Agogo mẹ́rin àbọ́ ti lù, àsìkó ti tó fún ẹ̀kà èdè Ọmọlúàbí ní oríi Bond 92.9 FM. #Yoruba #Bond929fm https://t.co/Srq1Yz1fhd | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ KÁÁRỌ̀ O... 😊 GBOGBO ILÉ ŃKỌ́? 🤷♀️ A Ò NÍÍ DÀÀMÚ LỌ́SẸ̀ YÍ LÁGBÁRA ỌLỌ́RUN! 🙏 (Good morning... How's your family? May we not be troubled in any way, this week, by God's grace) #yoruba #iwure #adura #ojumoire… https://t.co/AU6hWskinw | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ààrẹ ẹni tí wọn fún ni inagijẹ baba go slow ní kété to gorí aleefa látàrí aitete yàn àwọn minisita rẹ lo ti padà dá go slow sílè báyìí ni ìpínlẹ̀ plateau lónìí nígbà tó ń ṣe abewo pàtàkì sì ipínlẹ̀ náà | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìpìlẹ̀ tí ó pọ̀jù. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
ẹ wo yẹ̀yẹ́ àwọn aṣòfin ilé igbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ rivers gt | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òru là ń ṣ'èkà; ẹni tí ó bá ṣe é lọ́sàn-án ò ní fi ara ire lọ. #EsinOro🐎 #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ojúmọ́ ire ló mọ́n o. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọwọ́ ẹ̀rọ̀ ló bá dé àwọn aginișọ́ wá kí mi sílé òjò tó rọ̀ ló tì wọ́n sóde | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìgbẹ́kẹ̀lé tí àwọn afọ́jú #Paralympics ní nínú àwọn olùtọ́sọ́nà wọn mà pọ̀ o. Ìgbẹ́kẹ̀lé wa nínú Ọlọ́run yẹ kó rí báyìí, kó jù báyìí lọ! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
igi tó jóná tán ráúráú tó wá dàbí àtíkè kí la npèé eru | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
lọ́jọ́ kan ológbò sọ fún ọ̀rẹ́ẹ rẹ̀ pé káwọn jọ dẹ̀gbẹ́ lọ èkúté ní kò burú | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Oruko mi ni Lt Ibrahim Olanrewaju Bello. Abi mi si Surulere ni ipinle Eko. Omo Olorunda/Osogbo ni mi, lati ipinle Osun. #TweetinYoruba #BIO https://t.co/pznbZIDzME | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kò ní pẹ de àfojúsùn wá kò yẹ kó jẹ ìpè fún ìjọba tó fún àwọn ọ̀dọ́ láyé nìkan bíkòṣe eléyìí tí yóò mú àtúntò bá ètò ìsèjọba ìlànà àti àgbékalẹ̀ ìṣèlú tàbí ètò ìlú tó se gbára lé | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹni tí kò mọ bí ẹgbẹ́ rẹ̀ ṣe là, á sá àsákú. / Whoever unduly bothers about his or her peers' relative successes, will hustle himself or herself to death. [Compare yourself to no one; stay in your lane.] #Yoruba #proverb | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀nà là, ọ̀nà ọlà, ọ̀nà ọlá. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nígbàtí kò sí àbò ní #AsoRock bóo làbò ṣe fẹ́ wà ní ìlú? #GEJ #Nigeria | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ORAL POETRY AND THE PLACES WHERE THEY ARE RECITED/ EWÌ ALOHÙN ÀTI ÀWỌN IBI TÍ A TI Ń LÒ WỌ̀Ọ́N (2): The table below highlights the communities and the gender of people that take part in oral poetry Àtẹ Ìsàlẹ̀ yìí fi àwọn ìlú àti èèyàn tó ń kópa nínú àwọn ewì Alohun hàn https://t.co/O9vdjM7Psp | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: IPA TÍ ÀMÌ OHÙN-ÚN Ń KÓ NÍNÚ-U GBÓLÓHÙN YORÙBÁ Ní àkọ́kọ́, ẹni t'ó bá fẹ́ mọ àmì ohùn ọ̀rọ̀ èdèe Yorùbá dájú ṣáká bí ọṣẹ-… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
aku odun o e je ka ranti awon alaini bi a sense faaji | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Íṣe Olùdarí àkọkọ Akinnuoye - Agbaje je itan tí o bá ní nínú jẹ́ to dá lórí ìrírí Olùdarí náà èyí tí o jẹ ọmọ ti wọ́n 'gbìn jáde' ni Nàìjíríà lọ sí ìlú ọba ni asiko ìgbà kan . Wí wo ìgbà àkọ́kọ́ fíìmù yìí fi ibi ati òṣèré tí o ṣé gbàgbọ́ nípa wípé a ti ni ìrírí rẹ̀,ìgbà míràn yíò gbà ọnà ti o ni ìtúmọ̀ yíò fi ipá eni ... | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user ☺ e kaaro ! Bawo ni o se wa? #Yoruba @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀sẹ̀ kan ní ìgbésíayé àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè nigeria. Ó dára. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Eré ńlá . . Nípa ṣíṣe eré, Eré yìí jẹ́ òkan lára eré tó dára jùlọ tí mo ti wò. Ó mú mi rántí àwọn eré ayé àtijọ́ tí ó dùn tí ó jẹ́ tòótó. Ìtàn eré náà dùn àti wípé ó jinlẹ̀. Eré ńlá. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user Ẹ kú iṣẹ́ ma | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Èdè Potokí lẹ fi kọ ọ́ ni? Ọlọ́run ṣe é mo kúkú gbọ́ ìyẹn náà díẹ̀. :) | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìwé ìrìn àjò Olúfúnmiláyọ̀ ṣe. Olúfúnmiláyọ̀ pẹ̀lú àwọn aṣojú tí wọ́n lọ dúnà-dúrà lórí òmìnira Nàìjíríà. Ní àsìkò 1970, ó yí orúkọ rẹ̀ kúrò ní Ransome-Kuti, sí Aníkúlápò-Kútì Ní oṣù Èrèlé, 1977, àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà, ju Olúfúnmiláyọ̀ sílẹ̀ láti orí òkè, ní | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Koríko tí erín bá tẹ̀, àtẹ̀pa ni. Mo ti tẹ ìbànújẹ́ mọ́lẹ̀. Mo tẹ òṣì mọ́lẹ̀. Mo tẹ àìlera mọ́lẹ̀. Àìlówólọ́wọ́ ti di àtẹ̀pa. Àìsàn di àtẹ̀mọ́lẹ̀ jẹrà. Wọn ò tún gbérí mọ́, láé àti títí láé! #iwure | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kò sí bí ọmọ́ ṣe lè tètè jí tó oko ló máa bá kùkùté | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wọ́n á ki #Ibadan, """"""""Ìbàdàn m'esì ọ̀ gọ̀"""""""". Kíni ìtumọ̀ Oríkìi nì? Kí ni esi? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Seh nah """"""""Balogun"""""""" abi """"""""Otun"""""""" abi """"""""Asipa"""""""" abi """"""""Af'obaje"""""""" abi """"""""Ajir'oba""""""""?? Cute #Yoruba guy😍✊🏽 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ọ̀kan ń'nú iṣẹ́ ọnà ìbílẹ̀ ni ìlẹ̀kẹ̀ lílọ́, òwò tí ó lówó l'órí ni okòwò ìlẹ̀kẹ̀. Ìlẹ̀kẹ̀ tí a kó sínú àtẹ ìlẹ̀kẹ̀ máa ń kọ mọ̀nà, á tán jìngbìnnì jingbinni, papàá nínú òkùnkùn. Torí ìdí èyí, àwọn ọmọ Krìstẹ́nì Yorùbá mú àṣà yìí wọ ilé ìjọsìn. 💒 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Wọ́n dá obìrin sí, wọn pa ọkùnrin? Ó ṣe jẹ́ ọkùnrin nìkan? Ọ̀ràn ńlá rè é, ó fẹ́ ìwádìí tó kúnrẹ́rẹ́. #BokoHaram #YobeMassa… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àhunpò̩ ìṣé̩ ìmé̩lé̩ tí kí í ṣe ojúlówó ni "Social Media 101". Isẹ́ ọwọ́ àwọn tó ń ṣ̩e àgbélè̩ro̩ sinima ni èyí. Àwọn ló ń sọ isẹ́ onísé̩ di tiwọn. Àpẹrẹ sísọ ìṣe onísé̩ di tẹni ni "Social Media 101" jé̩. Kò sí àfihàn ọgbọ́n àtinúdá kankan ní́bè̩. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Moni gbagbo pe Thomas Lemar yoo di omo egbe agbaboolu Arsenal laarin Ose to n bo. #TweetYoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹjẹ́jí ájùmọ̀ gbé àsà wa lárugẹ #YORUBA https://t.co/ykIVMKsR9l | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
6. Mádàáríkàn ▶️ òògùn àjẹsára tí kì í jẹ́ kí àsàsí mú èèyàn Òkígbẹ́ ▶️ òògùn àjẹsára tí kì í jẹ́ kí nǹkan tí ó mú ó ṣá ni lọ́gbẹ́ Aṣaki ▶️ òògùn àjẹsára tí kì í jẹ́ kí____________ #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ kú àṣálẹ́ o ẹ̀yin tèmi :) | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọlọ́fin ni orúkọ oyè ọba Ifẹ̀ kí ó tó di Ọọ̀ni. Odùduwà ni Ọlọ́fin àkọ́kọ́. #idahun #Ibeere #Yoruba https://t.co/OwcIOnYiuK | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ní ayé àti àwọn ọba onípò ọlọ́la àti olóyè ni wọ́n ma ń tẹ́ ewé sílẹ̀ fún láti tẹ̀ kọjá | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user dada ni o, ko koja ifarada. A dupe lowo Oluwa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọyápidán Ọya makes magic. https://t.co/ZFOIv8RXFP | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ko ba emi na gbe oooo amin | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ewé kátabá. Ọ̀tá okùn-ilẹ̀. Àwọn #Yoruba máa ń gbin kátabá s'ágbègbè ilé wọn kí ó ba lé ejó réré. https://t.co/V8Lw79F1ar | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ gbé àṣà wa ga; #English nìkan kọ́ ni à ń kà nílé ẹ̀kọ́. @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.