text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
RT @user: @user Pepeye, Aguntan, Elede
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eré tí kò ní ìdí.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user Ẹ ẹ́ pẹ́ fún wa!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ó yá follow me back ẹ seun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ní òní nìkan ṣoṣo múrí mẹ́ta náírà lẹ ti gbọ̀n yọ kán mo ti sọ títí pàbo ni ó ń jásí kí ló dé ndan wọ́n bí ṣómi mẹ́ja ni
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹni mímọ́ Isrélì!. . Kínni Genevieve rò pé òún ṣe? Eré? Ìwà ìbàjẹ́ tó gajù ni èyí.. . Olùkọ'tàn naa kò dáa tó.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: """"""""@user: Chile ti ṣílé Spain | #Brazil2014 #idanoripapa"""""""" Oma se o. Se' Spain ni awon Chile wa n ko igi iya fun bayi?
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kòlè yé e yín àmọ́ mo mọ̀ wípé á á dára e lè dá promo dúró fún gbà díẹ̀ ẹ dákun ẹ mọ́ bínú ó kú díẹ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọlọ́hun kó wa yọ, gba wá lọ́wọ́ọ wọn. Àwọn afojú fẹ́'ni má f'ọkàn fẹ́ ni. #CentenaryAwards #Nigeria
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user bi e ti n pe mi ni mo n je, owo mi lo di die, mo se opolopo wahala lose yii
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹ mà kú ìdúrótì àti akitiyan nlá o. Iṣẹ́ gidi lẹ nṣe fún ìlú wa.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó sọ bí Ọ̀yẹ̀kú ṣe kọ́ ọmọ aráyé bí a ṣe ń ṣ'ètò òkú yíyà, pàṣán sì ni a fi ń na ilẹ̀ bí a bá ń ya òkú kúrò láyé. #Eegun #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ewé méjèèjì ni a fi ń wépọ́n ẹ̀kọ́ àgídí ewé gbòdògí ni a fi ń sín yí obì kí ó má ba à gbẹ sódì ewé eran máa ń gbẹ àmọ́ rírọ ni ewé gbòdògí máa ń rọ ní tirẹ̀ dídán ni ara ewé eran máa ń dán gbòdògí kò dán níṣe ló rí ràkọ̀ràkọ̀ ni
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ kú orí ire irú ẹ̀ la ó máa rí o àmín ► the most powerful women in global tv
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
onirinkurin ko ki se egbe oniwe mewa
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Akikiitan Eledumare, Alagbada nla, Asore kiri, saanu fun wa loni o. Amin.@user #aduraowuro,
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user naani naani naani, ohun a ni la naani. Tiwan ntiwa, teni nteni. A o gbodo ta lopo.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mo fi asiko yi kí gbogbo ọmọ ìjẹ̀sà nile loko in ra purẹkẹrẹ mọya o gbogbo ria laa kere oko dele hin pẹlẹ o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user mo fi owó 1200 fún #BBM #Social lọ́jọ́ Ọjọ́bọ̀, mo sì ń lò ó títí di ìrọ̀lẹ́ Sátidé tí n ò fi ri lò mọ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí tún ní í pànìyàn láì ṣekú? Ọ̀jẹ̀ Onímọ̀ Yorùbá yún'sẹ̀ òrìṣà. Ọ̀jọ̀gbọ́n Abọ́sẹ̀dé Olúwọlé ti gbé kiní ọ̀hún rọ̀run. Oṣù kẹsàn-án ọdún yìí l'ó pé ọdún kan tí mo rí ìyá níbi ètò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ nípa Èṣù tí a ṣe ní @user. Ikú dá Yorùbá lóró!
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀kan nínú òkú tàbí ààyè kakanfò gbọ́dọ̀ wọ̀lú láàárín oṣù méjì (ọgọ́ta ọjọ́). #AareOnaKakanfo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ijekuje o je ki e gbon se reluwe ti hitler lo ku ni enpon le ni ni ilu oyinbo ti eti wa se oko fakafiki ni wan nlo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Orúkọ ọmọ ni ìjánu ọmọ. #EsinOro🐎 #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user: @user amin e po, mo fe ran oun ti oun se...waju waju ni opa ebiti e a ma lo....oju mo ire mo wa ni o ni.""""Àṣẹ, á rí bẹ́ẹ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
tẹní bẹ́gi ló jù igi á rúwé
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Adéwálé Akínnúoyè-Agbájé, tí ó kọ̀wé, tí ń darí àti ní ìrírí irú iṣẹ́ àgbẹ̀ bẹ́ẹ̀ lákọ̀ọ́kọ́, sọ̀rọ̀ nípa ìwà ẹlẹ́yàmẹ̀yà tí àwọn ọ̀dọ́ wọ̀nyí bá pàdé, kí wọ́n tó wọ̀ wọ́n lọ́kàn délẹ̀délẹ̀ nínú eré orí awọ.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Omo Atiba.. Adebayo Faleti.. Baami sunre ooo. Eiye odede ba loru le.... oro ni eiye ngbo..... #yoruba #actors #theatre
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gbajúmọ̀ ọ̀rọ̀ Yorùbá yìí; MÁ SỌ MÍ DI ẸDUN ARINLẸ̀, jáde láti inú àrà tí Ẹdun ń dá. Ẹdun yára sáré, àti wípé, kò sí àrà tí wọ́n kò lè dá lórí igi. Ṣùgbọ́n, tí wọ́n bá dé orí ilẹ̀, wọ́n ma di ọ̀lẹ ni. Ó sì yára láti ṣe wọ́n ní jàm̀bá lórí ilẹ̀.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Oshi! Nkò lè sọ fún ẹnikẹ́ni nípa rẹ̀. Kò dá b'ó jẹ́ ọmọdé. Ère náà rínílára.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user Órò Ààre Trump ti di ká f'owó s'énu, ká dá'ké. Àfi bí àsàsí! Kó'dà, ó ti dá Améríkà padà sí ìgbà aìmò. Ó mà se o. #TweetYoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ọkọ̀ míì ò tiẹ̀ ní iná kankan. Ènìyàn á ti súnmọ́ wọn tán kí ènìyàn tó rí wọn.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
B'ẹ́nìkan bá sọ ìsọkúsọ ọ̀rọ̀ tí a ò leè fi òtítọ́ rẹ̀ mulẹ̀, ìbanilórúkọjẹ́, ó ní bí a ti ń ṣe é, a ti pèsè rẹ̀ sílẹ̀. @user #Nigeria
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹní fẹ́ ìdí ọ̀rọ̀ ní í wá ìdíi rẹ̀ gbọ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Toò. Wákàtí mẹ́rẹ̀rínlélógún kíní ọdún ti ṣojú wa. Ọlọ́run fún wa ní ore ọ̀fẹ́ láti rí ìyókù náà o. Àti jù bẹ́ẹ̀ lọ. #2013
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user @user @user Se """"""""@user lo ko owo Lora ota ibon ati ibon ni South Af…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
“@user: @user bi ako ba ri eni feyinti atera mo use eni.....
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ó dàbí i pé nkankan ló ṣẹlẹ̀ láàrin àti ṣẹ̀bí ti nrányàn lọ tẹ́lẹ̀ ó ga o
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwòrán yìí fi hàn ibi tí ìlera pọ̀ sí #BBC ~> #NationalConference #ConfabNG http://t.co/Oh8pzcgAX6
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user This are the names of #Months in #Yoruba: January: Ṣẹ́rẹ́, February: Èrèlè, March: Ẹrẹ̀nà, April: Ìgbé, May: Ẹ̀bibi, June: Òkúdu, July: Agẹmọ, August: Ògún, September: Owewe, October: Ọ̀wàrà, November: Bélú, December: Ọ̀pẹ̀. #RushHourShow
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Apẹ̀rẹ̀ ni ahunagbọ̀n ń hun, ère ni ti agbẹ́gilére, àpótí ni ti gbẹ́nàgbẹ́nà,_____ ni ti onígbàjamọ̀? #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kí lorúkọ ẹja inú àwòrán yìí lédèe yoòbá
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Oríkì kòrónà Amúni dúró nílé tipátipá Ẹkùn ọkọ olóṣèlú Nàìjíríà 😆 Ẹni àìrí sójú t'ó ń jà bí èpè Atúwọn ká níbi gbogbo tí wọ́n ń péjọ Ẹ̀rùjẹ̀jẹ̀ ní gbogbo ilékílé #COVID19 @user https://t.co/IfmgN2At7A
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Kábíyèsí, ẹni a fẹ́ la mọ̀, a kò mọ ẹni tó fẹ́ ni. Ng kò bá ẹnikẹ́ni ṣọ̀tá; síbẹ̀ ẹnìkan ṣáà gbé òkú sínú ṣọ́ọ̀bù náà. Kò…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Àgbẹ̀ tí kòkó ẹ̀ yè, kì í ṣe mímọ̀ọ́ ṣe rẹ̀, bíkòṣe Elédùà. A farmer with a thriving cocoa farm owes this not just to his eff…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ó di ọjọ́ kẹ́ta oṣù òkúdù kí a tó mú ọdún tuntun bí kọ́jọ́dá yoòbá ṣe tọ́ka
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìgbà tí mọ̀ndàrú bá ṣẹlẹ̀ tán, tí gbogbo ẹ̀ polúkúmuṣu, àwọn òṣèlú àti ológun tí wọ́n tì #BokoHaram lẹ́hìn á wá fẹ́ fìyen gbá'jọba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Jíjẹ àti mímu ní gbangba tàbí ní ibi ayẹyẹ lòdì sí òfin iṣẹ́ àwọn Ọba ní ilẹ̀ Yorùbá. Ibi tí ẹsẹ̀ ti pamọ́ tàbí ibi ìkọ̀kọ̀ ni ọba ti ń jẹ, tí wọ́n sì ti ń mu.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Bí wọn bá fẹ́ fi èrò ọkàn wọn hàn elòmíràn, wọn níláti fi orí wọn kan ti olúwarẹ̀. #TweetYoruba #ItanEde
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àsọdùn, kò sí ìdarí
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Mo ní ìfé ẹ pátápátá. . Àti wo àwọn fíìmù noliwudu ke sábà yá sí mi lára ṣùgbọ́n eléyi je ọ̀kán pàtó tí èèyàn kò lé má wò àgàgà tí o bá féràn ìfẹ́. A to ìtàn náà dáradára, àwọn òṣèré náà ṣe dára dára. Eré eléyìí jẹ èyí tó ma wò ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà. Mo Orí yìn fún gbogbo àwọn tó kópa nínú eré yìí. Ó mo ri mi wu.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ẹkùn alábẹlọ́wọ́ náà ó fi bẹ́ẹ̀ kùn nínú igbó àti pé igbó tí yóò ti kùn dà láyé tí a wà yìí àwọn apẹranjayé ti pa kíkùn m
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
I wonder? #Yoruba """"""""Eko odi"""""""" https://t.co/nswc4BbHif
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ ṣé ìyá mi ❤️ 🖤 https://t.co/dVoQspNuR1
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹranko wo ní ń jẹ́ lárìnká? Kí ni ṣe tí a fi pe ẹranko ọ̀hún ní lárìnká? #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Iya afin @user so wipe a won kole raye da awon ololufe won lohun leni nitori wipe,won fe lo se oge ijade.#TweetinYoruba #Osexyfriday
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn dìndìnrìn kan á ní a ò ní ìtàn àkọsílẹ̀; òwe, oríkì, ìjálá, ìyèrè Ifá ńkọ́? Àwọn wọ̀nyí kún fún ìtàn-an wa
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Aseee""""""""@user: Ọjọ́ tó kẹ́hìn ọdún un #2013. Àwa yìí yóò rí òní jálẹ̀ lọ́láa Ọba Òkè. #Ekaaaro""""""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Happy Birthday to u wuraolaabosede09 Igo loju afi bi afoju. I wish you long live and prosperity #remmychanter @user mcefcc #nairablink #yoruba #oriki #orikiiresa #ibile #ewi #ijala #ekuniyawo #kakakiode https://t.co/RiQBhItIo0
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ohun tí mo yàn láti dà ni mo jẹ́, n ò kí ń ṣe ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí mi"""" - Carl Jung #TranslatedQuotes #AnyQuoteInYoruba #RandomQuotes #RandomThoughts #Quotes #YorubaTranslator #IyaYoruba https://t.co/LXsjzGX9Dz
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn àyíká tó dùn, ìwé búburú
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ẹ kú ọdún o gbogbo ẹlẹ́sìn mùsùlùmí ọdún alálùbáríkà ni yóò jẹ́ o àṣèyíṣàmọ́dún o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kí ni ìyàtọ̀ tó wà láàárín igún àti àkàlà what are the differences between the buzzard and the vulture
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ogbeni @user se eti ri fideo ti won ti paruwo ole! jaguda! mo yin lori? Eje so ewe gbe je mowo ki e ma ba te https://t.co/fqAKH3spAS
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
14. Kọ́léoṣó ń mí gúlegúle Ọ̀pẹ́féyítìmí ń làágùn ____ Ìgalà náà bẹ́ kẹ́ṣẹ́kẹ́sẹ́ #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bó sewà, kò láyè tàbí ìwà torí aní làti se oun púpọ̀ kóbalè wọlé tán
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Ọmọ àlè ní í fi ọwọ́ òsì júwe ilé bàbá ẹ̀. #SpeakYoruba #learnyoruba #language #InYoruba #Yoruba https://t.co/f93MGlMLdE
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ase wa. Ati emi na ooo""""""""@user: Ǹjẹ́ ayé mi á dùn bíi ti ìrèké, adùn l'á á gbẹ̀yìn ewúro tèmi. Àṣẹ! #Ojo #Ireke #Ewuro #Yo…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọ O'òduà! Bí o bá mọ b'órúkọ #Yoruba kan ti ṣe ṣẹ̀, ìlú tàbí ìdílé tí ń j'órúkọ ọ̀hún, kàn sí kt@user.com @user @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ỌDÚN ÀTI AYẸYẸ NÍ ILẸ̀ YORÙBÁ: ỌDÚN ÈṢÍ: ayẹyẹ tí wọ́n ṣe ní ọdún tí ó kọjá (ní ọdún èṣí) ỌDÚN YÌÍ: ayẹyẹ tí wọ́n ma ṣe ní ọdún tí wọ́n wà nínú rẹ̀ lọ́wọ́ ÀMỌ́DÚN: ayẹyẹ tí wọ́n ma ṣe ní ọdún tí ó ń bọ̀ (àṣe yìí ṣàmọ́dún)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eré tíkò ní ìtumọ̀. . àwàdà leré yí
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ó ṣe ètò àti ẹ̀rọ títa omi láti ilé rẹ ní ìjú ní ìgbà àsìkò lọ òwò omi títa gbayì ó gbẹ̀yẹ tí èrè orí rẹ̀ pọ̀ ní rẹpẹtẹ títí ìjọba fi bẹ̀rẹ̀ si ní ṣe àkóso omi títa fúnra wọn da rocha ṣe òwò wúrà ní ọdún tí ó sì rí èrè jaburata ní orí rẹ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí ni k'á ti pe ti ọ̀kan-ò-jọ̀kan iṣẹ́ ọnà tí a tà lọ́nàa pàsípààrọ̀ láàrín abúlé, ìletò àti ìlú aládé etílé àti jínjìn. #Kiwontode
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Yàrá kékeré gba ogún ọ̀rẹ́, tí ìfẹ bá wà láàárín wọn. / A little room is sizable enough for twenty friends, if there…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ gbọ́ o dòdò ni kí n fi ọ̀gẹ̀dẹ̀ yí ṣe ni àbí bọ̀ọ̀lì
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ mà kú ọjọ́ mẹ́ta o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìlọsíwájú kò ṣe dáradára fún díẹ̀ nínú àwọn ìwòyè náà.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Bí a ṣe gbọ́n nílé alárinà, la gbọ́n nílé bàbá ọmọ. #Yoruba #EsinOro🐎 https://t.co/fd9BvK0Ihg
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Lá Lálẹ̀ ẹrẹbẹ̀, Ẹrẹbẹ̀ Lálẹ̀! #laleerebe #iyil2019 #indigenouslanguage2019 #kengbeoro #africa #culture #nigeria #yoruba #igbo #hausa #ghana #gbajumoÒṣeré… https://t.co/OWH92AOYZi
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí ayé bá ń yí, ká máa bá wọn yí. Lóòótọ́ ni, àmọ́ ká lo ọpọlọ, ká má gbàgbé, ká rántí ọmọ ẹni tí à ń ṣe. #KoOrukoDaadaa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Láì sùn, láì wo. Alálẹ́ yìí ṣe é l'á ṣe pé. Kò máà jẹ́ àṣedànù, àfi àṣeyege, àṣeyọrí sí rere, nítorí àṣeyè ni alákàn ń ṣepo, àṣẹ iyọ̀ ni iyọ̀ fi ń já'bẹ̀, àṣẹ òṣùpá ni òṣùpá fi ń mọ́lẹ̀, àṣẹ wáà wáà ni ti ìrèké. Ọ̀ṣẹ́ẹ̀turá gbé e lọ sílé àṣẹ!!!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀nà tí èèyàn tọ̀ tó ṣubú, bí èèyàn bá ní sùúrù, èyàn lè tọ̀ ọ́ là. / A path that one treads and fails, with patience, one may tread it to success. [No closed case and nothing is impossible; be patient and persistent.] #Yoruba #proverb #BBNaijaEviction #Bbnaija #TeamMike
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Big fat lie', kò panilẹ́rìn, kòsì tó ojú òsùwọ̀n
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Ẹ̀yin ọmọyè mi, àbí ẹ ti sùn! Ẹ jẹ́ ká gbìyànjú láti máa fọ èdè Yorùbá lójoojúmọ́. #TweetYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
sùgbón o ká mú tàwàdà kuro awa obinrin maa n saponle okunrin tó ba fé wa tinútinú ó maa n jeyo nínú sí
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ó lómi nílé fẹ̀jẹ̀ wẹ̀ ògún a wọ́n lẹ́yinjú ègbè lẹ́yìn ọmọ kan oníjàoòle ẹjẹmu olúwọnran a dì gìrìgìrì rebi ìjà
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user: @user modupe fun oba oluwa.""""tala ò bá tún dúpẹ́ lọ́ọ́rẹ̀, bíkòṣe Ọba Adániwáyé :)
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Amin! Ko si oun to soro fun Eledua@user @user @user @user @user @user
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
etíi wa ò ní gbọ́ọ̀gbọ́ kúgbọ̀ọ́ ìròyìn ayọ̀ ni etíì mi á máa gbọ́ etí mi ò ní di bíi ti ikún etí mi a gbọ́re lónìí ẹtì
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ǹjẹ́ o mọ̀ pé orúkọ ẹrú plasido ni ẹbíi gbajúmọ̀ agbẹjọ́ròo nì adéyẹmọ alákijà ń jẹ́ tẹ́lẹ̀ kí a tó yíi padà lọ́dún un
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
My Village People ni àwọn isé sinimá tó dára kan tí wọn kò sì ní àṣejù. Ara àwọn isé yìí ni òjò náà. Àwọn onímọ̀ ẹ̀rọ náà yẹ fún ìgbóríyìn fún iṣé takuntakun tí wọ́n ṣe.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
àwọn tó ń mú igbega bá àṣà àti ìṣe yoruba lọ́nà iwuri baba suwe babatunde omidina ti gbogbo ènìyàn mo sì baba suwe bí wikipedia ṣe sọ a bíi ni ojo méjìlélógún oṣù kẹjọ lagos island nigeria
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Àgbà ní í pa òwe.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Are you from Lokoja? cause ti’n ba fe lo, mo lati koja e 😂 #pickupline #yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ kú ọjọ́ ìbí orí twitter o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user o ye ki awon dockita ti se aiyewo #Ebola fun gbogbo wo #IdanOriPapa
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
.@user @user @user A ò lo Ináa mànàmáná dójú àmì, ìyẹn ò sì ní kí Adámú yín ó máà mú ìwé owó iná wá. Ìyẹn ò rá a yín, àfi kí ẹ gba owó ìbànújẹ́. #KoSinaKoSomi
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
asejù ni olorun ajanaku oniduro mi ti wa okay | | |
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
6. Kín ni à ń pe ẹranko yìí? #ibeere #Yoruba https://t.co/SK5YZ4RBdK
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""@user: Asín òun Èkúté jọ njà."""""""" Asin oun okere ni won fi ko wa ninu Alawiye oh.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
wo ewì ọmọge ìwòyí tí mo kọ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train