text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
gbogbo ènìyàn ni a bí ní òmìnira iyì àti ẹ̀tọ́ kọ̀ọ̀kan sì dọ́gba wọ́n ní ẹ̀bùn ti làákàyè àti ti ẹ̀ríọkàn ó sì yẹ kí wọn ó máa hùwà sí ara wọn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìyá | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìtàn náà kò kún tó, kò pani ní ẹ̀rín | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Nijeria aku odun o! A gba ominira lowo awon alawo fun fun. Awa dudu wa hun gun ara wa bi esin. Koda oko eru Oyinbo wa da bi paradisee . #54 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user mo Mo ngbọ́ orin yín """"""""Bimpé"""""""" lọ́wọ́ lọ́wọ́ báyìí ó sì npamí lẹ́rìn-ín. Àwọn èyàn nwòmí pé kí ló nṣe bọ̀bọ́ yìí :)) | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nitooto, àwòrán tó dùn wo tí ó sì yanilenu. . . Ina náà àti, ìṣeré àti àwọn ohun èlò ìṣeré náà lewa púpò. A lè fi eré yìí sí ẹka àwọn eré ayé òde òní. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
RT @user: """"""""@user @user Baba olowo Chelsea Abramovich le gba Mourinho pada lati odo Real Madrid ni ofe http://t.c… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ó mọ ohun tí ó fà á ó sáré lọ sí inú oko ata kan | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: @user kini Palm ni ede ibile wa o?"""" #tweet mi tó kẹ́yìn - ọ̀pẹ #Palm #InYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Aṣèbàjẹ́ ò ní gbayì. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#iroyin, #yoruba, Odaju lawon gomina ti won je awon osise lowo osu - Aare Buhari: Tolulope… https://t.co/EuezKxnCDi | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ kú ìtọ́jú máa kọrin arẹmọlẹ́kùn fún adérìnsọ́lá kí o máa gbé e jó kí wọ́n fẹ́rànan rẹ̀ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: @user amin, pelu awon ti won fe wa d'enu""""àmìn àṣẹ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó ṣe, ọ̀pọ̀ wọn ti gbàgbé ẹyẹ t'ó ṣu wọ́n, wọn ò rántí bí bàba bàba bàbáa wọn ṣe dé ibẹ̀, wọ́n gbàgbé ilé. #AfrikaDowoWa | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
oda bee oni yoo san gbogbo wa si owo si omo si aiku baale oro ọpẹ́ ni fọ́lọ́run | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
3. Amore lo koko tedo si Ilu ti a mo si Ikeja l'oni. O wa lati Ota ni gba to n wa Ile ti yi o fi da'ko. #TweetinYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Oníṣẹ́-ìròyìn ní Nàìjíríà: 1.Agbébọnrìn pa Lawrence Okojie ń Benin ń'nú oṣù Agẹmọ 2017. 2.Ọmọẹgbẹ́ ọkùnrin 7 dìgbòlu oníròyìn… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọlọ́rùn-un mi ò !!! Mo ní látí dá KOB dúró láti sọ nípa eré orí ìtàgé yí. Olùkọ ìtàn tó Mọ́ṣẹ ni ọ́. Eré náà wú ní lórí ósii sí ní lójú. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Wọ́n ní kí ó rú aṣọ dúdú kan, Bùjé díẹ̀, ìpẹ̀pẹ́ irin, màrìwò ọ̀pẹ̀, Àti ewé ilá ìròkò. Gbogbo rẹ̀ náà ni Ògún rú. Àwọn awoo rẹ̀ẹ́ wá ní kó gbé ẹbọ náà lọ sí ààlà oko Níbi tí àwọn àgbọ̀nrín gbé ń jẹ. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn ti àdó olóró #BokoHaram bá lánàá, a bá wọn kẹ́dùn. Olúwa tù wọ́n 'nú. Olódùmarè dáàbò bo àwa ìyókù. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""@user: Ire gbogbo lo ma ba mi. RT @user: Ire mi kò ní rékọjá mi o. Ẹ̀yin nkọ́?"""""""" ire ni temi loni! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹni tí ń fi ilà kíkọ ṣiṣẹ́ ṣe ni olólà | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user ṣe àlàáfíà ni? ṣe òpin ọ̀sẹ̀ dùn? | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọlọ́fin ni orúkọ oyè ọba ifẹ̀ kí ó tó di ọọ̀ni odùduwà ni ọlọ́fin àkọ́kọ́ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
baba ti wa fi na sori orule sun bayi o pelu gbo gbo ogun abele ti o de ba egbe oselu nise ni wan fe ko si oko balu lati lo sinmi ni ilu oba fun ojo mewa gba ko | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Olubadan of Ibadan land, Oba saliu Adetunji (Aje Ogunguniso 1) Showers Blessing on Me. #2019 #mustobey #amen #yoruba #culture #tradition #elder #courtesyvisit #celebrity #arrival #king… https://t.co/4jdj2covtx | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ọlọ́run á fún yín ṣe o. Óyá ṣé ẹ lè tún un sọ ní èdè Yorùbá? | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí á di ìdí kó kún bámúbámú A díá fún ataare Tí kì í di ẹrùu tiẹ̀ Láìkún ọ̀kẹ́. Ǹjẹ́ igba orógbó Igba ataare Igba ẹyọọ rééré Igba ọkàa bàbà Ta l'ó pé Òdí 'ò lówó l'ọ́wọ́? #Iwure | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kè é ṣẹ̀hìn tí krìstẹ́nì dé la bẹ̀rẹ̀ sí í pe ọjọ́ lọ́jọ́ ọ̀sẹ̀ àyálò èdè ni ọjọ́ọ̀sẹ̀ ọjọ́ àkọ́kọ́ ọ̀sẹ̀ fún | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
15. Kíni ìtumọ̀ àjàm̀bàkù? #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Láìsí ìtọ́sọ́nà àti ìtumọ̀, eléèyí jẹ́ kan tó gùn , tó le tí yóò ti ò fi le dára níwájú àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí tí àwọn tí olùdarí àti àwọn òṣèré. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ní ọlá ọlọ́la, a ó sọ ìtàn kan tí ó dòwe. Ṣé o mọ Òkòló? #ItanDowe #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó dà bíi wípé àwọn ọmọo wa ńta bíọ́bíọ́, pẹ̀lú ariwo yìí #nigeria | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó mó rí wu , ósì pa ni lẹ̀rín bi wón ti ṣàpèjúwe àṣà méjèjì. Mo ni idálaráyá jálè ! Erè àgbéléwò to jágeree ní è yìí. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Orí mi wú 😊 https://t.co/VBvnXGi3KG | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ ṣeun baba fun ojo oni | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ̀kọ́ àti ìdanilẹ̀kọ̀ọ́ ló ń mú ìdàgbàsókè wá > #Mikheil #Ehingbeti2014 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
gba bee rt ìfẹ́ ló ṣe kókó ìfẹ́ sí ọlọ́run rẹ àti sí ọmọnìkejì ́ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Gẹ́gẹ́ bíi olóṣèlú alátakò, àwọn òṣìṣẹ́ ọba ti fi hàn wípé àwọn gan-an ni adárúgúdù tí ó ń dá àhesọ àti ọ̀rọ̀ ìkórìíra sílẹ̀, tí ó ń lo ẹ̀rọ-alátagbà fi dá rúgúdù sílẹ̀. #NigeriaDecides2019 https://t.co/PZ8u5mOrcM | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ehín t'ó tatayọ ẹnu; wàhálà ẹnu ni #Owe #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Kò tọ́pẹ́ o. A kìí dúpẹ ara ẹni. :) | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òwé kan ní pé """"""""òkú olówó ló ńsun orí ìtẹ́"""""""" báun gẹ́lẹ́ ni tọba aláṣẹ igbá-ìkejì òrìṣà rí #IsinkuOba #Alade #yoruba #owe | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bí ẹ̀mí ṣì wà, ìrètí ṣì ń bẹ. Ẹdìẹ tí ò kú ṣì máa jẹ àgbàdo. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ojú mi rí nǹkan n ò ní í sọ ọ́ lónìí mo wòran láti aago mẹ́rin di mẹ́fà kí n tó gba ilé ìtura tí mo gbà lọ sinmi | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
omo yorubá ni moję mo wà ni nigeria nítorí wípé èyà kan kò lè dá orilèidè şe https | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òjògbón @user, báwo ni a se leè pe ipò Statistician General ni èdè Yòrùbá? #TweetYoruba @user @user e bá wa dá s'órò yí o. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ kú ojúmọ́. Ẹ kú ojúmọ̀. Ẹ kú ojúmọmọ. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user Nígbà tí ìran sú mi íwò, tí òrùnrún ti pa kísà sí mi lára, èmi àti olórí-ẹbí Ayọ̀adé Ẹlẹ́rẹ̀ Àdùbí jọ kúrò níbẹ̀ láago méjì àbọ̀. Èkó yá! | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àpọ́nlé ni riri nínú """"""""Ó dúdú riri"""""""", kíni ọ̀rọ̀ àpọ́nlé fún pupa? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fíìmù dídọ̀tí . . Kòsí ẹ̀kọ́ kíkó kankan. Ẹjọ̀ọ́ afẹ́ apá kejì | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
wọn yóò ru gbogbo rẹ̀ lọ sínú igbó tó dúdú birimùbirimù inú igbó dúdú yìí ni a ó ti ṣe ètùtù náà | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹsẹ̀ Ifá yìí ń ṣàlàyé ìrísí ẹyẹlé àti bí ó ṣe jọ àdàbà àti Oori. Ó ṣàlàyé pé ẹyẹlé kì í tóbi jura wọn lọ. #BiEyekoSeDiEyele #Yoruba #Ifa | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Bẹẹni... Òótọ́ ni Odídẹrẹ́ ma ń sọ ní gbogbo ìgbà. Ìdí èyí ni wọ́n ṣe ṣọ́ ní Aiyé kòótọ́ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
3. Igi = gbẹ́nàgbẹ́nà Irin = àgbẹ̀dẹ Irun = ____________ #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ yẹ ọmú wò, ṣé ó wà b'ó ṣe yẹ ó wà? O kò ṣàkíyèsíi nǹkan àjèjì? Ẹ tọ́júu rẹ̀ o. Torí ... #AyewoOmu | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ẹ gbayì jàre | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Iyà l'olùgbowó mi tí n tójú mi ni kékeré... Eyìn re lo fi pon mí.... Èmi íkí 'ya mì kú 'sé.. Èmi kò lè ko'sé fún 'ya mì. ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wọmbiliki-Wọmbia is the word for unredeemable glutton in Yorùbá Language. . Yorùbá is fún to learn. . #babayooba #yorubalanguage #learnyoruba #learnyorubawords #yoruba #yooba https://t.co/cSJns6Y2Je | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user odabi aláwada ori itáge @user lo sọ ọrọ yi abi irẹ lo ro kọ? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Big Cat Lie' kò ṣe aláìpani l'ẹ̀rín lásán, kò bá ìgbà mu náà. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user Àní ká fi ọ̀rọ̀ ọ̀hún mu tábà ní gbẹ́rẹ́fu. Ọ̀rọ̀ burúkú tòun tẹ̀rín. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Irú eré tí ó wuni wò ni èyí? Gẹ́gẹ́ bíi fífi ìfẹ hàn àti ìtàn, ní ìdàkejì, ó panilẹ́rìn-ínó sì wà pẹ̀lú àjálù, ó kún fún ìfojúsọ́nà àti ayẹyẹ ṣíṣe, kò sì ṣàìdánilárayá lákọ lákọ. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ẹ kú làákàyè @user @user @user @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user, àhesọ kọ́, R.H Stone èèbó #America òṣìṣẹ́ ijọ́ Baptist tí ó wá sí #Ijaye ní nǹkan bí 1859; 1860 fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀. #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹṣin ọ̀rọ̀ ní àdàbà kekelúke kò sí ọjà tí kò ná tán àpèjúwe nǹkan ni ọjà tí kò ná tán àmọ́ kí ni àdàbà kekelúke inú òwe yìí a ẹyẹ b owó ẹyọ d aláròró | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn kan ò ní'ná. Àwọn kan tan'ná sílẹ̀ yan-yan. Ìka ò dọ́gba. #NEPA http://t.co/2dqVbWhD | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ǹjẹ́, ẹ ò rò wípé, àtúnkọ rẹ̀ láti Gẹ̀ẹ́sì sí Yorùbá, kò ṣe ìdàgbàsókè fún èdè Yorùbá àti ìdàgbàsókè èdè náà? Don't you think a rewrite of it from English to Yorùbá doesn't help the growth of Yorùbá language? The name could reflect its function. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ṣẹrẹ, Èrèlé, Ẹrẹ́nà, Igbe, Èbìbí, Òkúdù, Agẹmọ, Ògún, Ọ̀wẹwẹ̀, Ọ̀wàrà, Belu, Ọ̀pẹ. @user #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: @user:ni ijapa ba paa'lori #lobatan""""bẹ́ẹ̀ni, olójúkòkòrò nìjàpá #itan #ijapa #tiroko #oko #yanrinbo #yobamoodua | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ajé Ògúngúnnìsọ̀! Ajé Ògúngúnnìsọ̀! Ajé Ògúngúnnìsọ̀! Ajé kú ojúmọ́ o. Ajé mo pè. Wá jẹ́ mi l'óhùn. Ajé mo pè. Wá k'á jọ máa gbé. Ajé mo pè. Wá dúró tì mí. Ajé máa bọ̀ níléè mi tààrà, kí o máà lọ sí ibìkankan mọ́n. #Iwure | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ojúmọ́ ire o. Ṣálàáfíà ni gbogbo wa wà? #Ekaaro | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user Toò. Arábìrin wa. Afẹ́fẹ́ ti fẹ́ a ti rí fùrọ̀ adìẹ o :D | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
wọn yóò wá tàgíìrì a ó rẹ́ ẹ sómi pẹ̀lú iyọ̀ diẹ̀ láti fi yọ irun ara awọ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user @user Ẹ kú ìgbádùn o :) | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ajá mọ ọmọ tirẹ̀ í fún lọ́mú; ó mọ ti odù ọ̀yà í kì mọ́lẹ̀. Kíni odù ọ̀yà? #ibeere #Yoruba #Owe | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#iroyin, #yoruba, O ga o! E wo iye owo osu awon osise kaakiri agbaye: Tolulope Emmanuel… https://t.co/IwG51m2CHR | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
owó yapa gt | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ijebu Omo alaare, ewe soo RT @user: @user @user ijebu ni rome wa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
pàsípaàrọ̀paàrọ̀ = exchangebarter wọn ò ní fi orí mi gba paàrọ̀ my head destiny shall not be exchanged | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user tí yàn obìnrin láti ẹyẹ tí o pọ tobe tó tún jé Mùsùlùmí gege bí igbakeji rè wọn pé ní onímọ̀ tara ẹni nìkan, ṣùgbọ́n nígbà tí @user yàn eya igbó Mazi Obi gẹ́gẹ́ bí igbakeji ààrẹ dípò Yorùbá @user wọn sọ fún wa pé """"""""KÍ WÁ LÓ FI Ń ṢEYAN"""""""" https://t.co/lyhA80YnbP | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
1. Ìkòkò dúdú fìdí t'ìgbẹ́. Kí ni o? #AloApamo #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
15. #PariOweYii Ẹni oòrùn kò pa, tí òjò kò pa... #Ibeere #Yoruba #Owe | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
oṣó yí mi ká | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ère yìí dà bí oun tó ṣekú láti ayé àtijó. Ìf'owósòfò pátápátá. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
orí ni àwúre orí máà padà lẹ́yìn mi máà jẹ́ kí n rówó sá tilẹ̀kùn òṣì kí o ṣílẹ̀kùn ọrọ̀ orí gbé mi délé owó kí owó bá mi gbé títí di ọjọ́ alẹ́ nítorí ojú owó kì í pọ́n dàda kí n di olórúkọ tuntun bí ọmọ tuntun kí n di ajénifújà | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user - Àní mo fẹ́ràn àwòrán etí òkun ẹ̀yin t'ìyáa yín lórí ẹṣin yìí pọ̀. Àwòrán tó rẹwà ni :) | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ní atetekọṣe ọlọrun dá ọrun ati aiye who | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
NAME IT / SỌ Ọ́ LÓRÚKỌ What Yorùbá name would you give the Scrabble game? Doesn't have to be borrowed. But, something indigenous. Orúkọ Yorùbá wo ni ẹ lè fún eré ìdárayá ọpọlọ yìí? Kò pọn dandan kí ó jẹ́ ọ̀rọ̀ àyálò. Ṣùgbọ́n, kí ó jẹ́ orúkọ Ìbílẹ̀ https://t.co/2oxlGChpWz | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ KÚ ÀÁRỌ̀. 😊 ṢÉ ÀLÀÁFÍÀ NI? 🤷♀️ OJÚMỌ́ IRE LÓ MỌ́ WA LÓNÌÍ O... Ọ̀SẸ̀ YÍ Á YA'BO FÚN GBOGBO WA! 🙏 (Good morning. 😊 How are you? 🤷♀️ Today is a good day... May this week be positive for us all!🙏) #yoruba #iwure… https://t.co/d5G2YjBki6 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìjánjá ẹran yàtọ̀ sí ìjànjà ️ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìtàn kò lábara, bẹ́ẹ̀ni àwàdà kò burú jù. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Yàtọ̀ sí irun dídì àti kíkó, irun bíbà pàápàá ò gbẹ́yìn. Àsìkòo pàjáwìrì ni àwọn ìyáa wa ma ń ba irun wọ́n bí wọn kò dìí. #AwaLaNiIrun | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òwe àwọn àgbà ní, """"""""Igi gbígbẹ ò ṣe é tẹ̀ ní kọ̀ngọ́."""""""" Ọmọ Yoòbá, jọ̀wọ́ kí ló ń jẹ́ kọ̀ngọ́? #Ibeere | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Oda binpe orun wa loju mi, mofe sun. #TweetinYoruba #BIO | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#Layajoaoni lodun 1987 Donald Trump gba odidi oju ewe New York times kan lati bu orileede Japan | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Yorùbá word of the day """"""""Dúró dè"""""""". #yorubawords #yorubalessons #yorubaforbeginners #languageclass #waitforme #InYoruba #LanguageLearning #Yorùbá #WordOfTheDay #iyil2019 #indigenouslanguages https://t.co/LIqBWQOLa3 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo fẹ́ dà bíi olúwo Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ b'ó lọ́la. Ọmọ Yorùbá àtàtà. #Awo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀wọ́n l'orúkọ tí à á pe Ọ̀wọ́nrín. @user #Ifa #Odu #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
✅Ọ̀bẹ ń wó ilé araa rẹ̀, ó ní òun ń ba àkọ̀ nínú jẹ́. ✅Àdá l'ẹnu tálákà, igbó la ó fi dá. ✅Bí ọwọ́ ẹni ò bá tẹ èkù idà, kì í béèrè ikú tó pa baba ẹni. ✅Ọkọ́ kì í kọ ju ilẹ̀ lọ. #InYoruba #learnyoruba #Language #Yoruba https://t.co/wGgh6e2v3s | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user @user Bí a bá dá igba odún ojó á pé. Òla lo jo pé #Yoruba https://t.co/87m6IX5LjD | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user @user @user @user oselu igbalode lofa ti oba fi so ara won di gbewudani laye ode oni | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.