text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
nje e ti gbo pe apa kokanla yeepa ti di bale gude lori | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Pánsá ò fura, pánsá já siná, àjà ò fura àjà jìn; onílé tí ó bá fura, ogun ní ó ko lọ. #owe #Yorùbá | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ ó lọ ẹ ó bọ̀ ẹ ò ní bọmọ jẹ́ o ire níwá ire lẹ́hìn ire lọ́tùnún ire lósì | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Hmmm... Ọ̀rẹ́ á ma tan ni pa nítorí ọrọ̀ 😪 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó àti Èkìtì yà ọ̀la sọ̀tọ̀ fún àyájọ́ #June12 #Ekiti #Lagos #Nigeria | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Sinimá tí kò dùn rárá tí àwọn òṣèré inú rẹ̀ kò tún wá ṣe daádaá. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user @user Toò. Ìpàdé wa bí oyin o. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí ni ìwúlòo ayárabíàṣá fún ọmọ̀'lé ìwé? Ẹ fún wa lápẹ̀ẹ́rẹ̀ méjì. @user #IAFEE | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Alafia ni o""""""""@user: Ẹ gbọ́ kí ló ju owó lọ ní ilé-ayé?"""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ibo odun 2015: Awon oloselu koju ija buruku sira won http://t.co/8L9fs0rfuc | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
abi e ma gbo oro rirun e oni se iwadi finifini ki to gbe ejo lo si ile ejo omugo leti e pe wani agbejoro yin o gbono ra ra | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
olorun to funmi lojo gbogbo lati yo god that gave me everyday to celebrate sunday | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìbínú ò da nǹkan; sùúrù ni baba ìwà; àgbà tó ní sùúrù, ohun gbogbo ló ní. Anger yields nothing; patience is the epitome of good character; an elder who has patience (as a virtue), already has all things. [Patience is superior to anger, and more effective, by far] #Yoruba #proverb | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
1. Irú èèyàn wo ni à ń pè ní abiagba? A. Obìrin B. Obìrin tí í ṣe abiamọ D. Obìrin tí kò ṣabiamọ #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ebi ń pa mí, kìí ṣe ohun àá sín gbẹ́rẹ́ sí. Àkàṣù ẹ̀kọ ló lè yanjú ẹ̀. Hunger is not something you make an incision on. Only a """"""""solidified pap"""""""" can solve it | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
E̟nì kò̟ò̟kan ló ní è̟tó̟ láti gba iye owó tí ó dó̟gba fún irú is̟é̟ kan náà, láìsí ìyàsó̟tò̟ kankan. E̟nì kò̟ò̟kan tí ó bá ń s̟isé̟ ní è̟tó̟ láti gba owó os̟ù tí ó tó̟ tí yóò sì tó fún 2/3 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àrọ́mọdọ́mọ kìnìhún nígbó ọmọ akọ ni ̀bá | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kì n ṣe pé gbogbo rẹ̀ ni ò kùnà lẹ n kanna, ṣugbọn bí àwọn tí wọ́n kó fíìmù yí jọ pọ̀ ṣe sọ àfojúsùn wọn nù tí wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí ní mú àtamán mọ́ àtamọ̀n tí fíìmù Nọ́líwuùdù ṣe wáá dàbí fíìmù Bọ́líwuùdù ní gígùn láìsí ohun tó ní láárí kan gẹ́gẹ́ bíi áwí jàre. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Láti ìjẹ́rin làwọn èèyàn ti ń súré kiri lọ́sàn-án, ariwo tatapùpù ò tún jẹ́ kí a sùn lálẹ́. #JakandeOkeAfa @user @user | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ǹjẹ́ ìwọ mọ̀ wípé Àdùnní Olúwọlé ni obìnrin àkọ́kọ́ tí yóò jẹ́ olùdásílẹ̀/olórí ẹgbẹ́ olóṣèlú ní Nàìjíríà? Ẹgbẹ́ K'óyìnbó… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
1. Yàtọ̀ sí k'á sọ wí pé """"""""ìró ìbọn"""""""" (gun-shot) tí í ṣe ọ̀rọ̀ àfidípò, gbólóhùn wo tún ni a lè lò? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ara ń fẹ́ 'sinmi. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Imototo bori arun mole bi oye se n bori ooru http://t.co/YfA2xHo1 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí ìbọn ó tó gòkè odò, oje ewé-iná ni a fi í kan orí ọfà tí ọdẹ ńta lu ẹranko igbó. Oró ewé-iná máa ń jó 'ni tí a ta á sí. #Yoruba #Ewe https://t.co/bH0lJag8i2 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Tani tabi Kini oke nla ti o do ju ko o bi iṣoro/idaamu/Apata ninu aye ati ẹbi rẹ, Olodumare yoo fi gbogbo wọn le ọ lọ wọ ni osù yii ni Orukọ Jesu. Iwọ yoo jẹ #StrongerThanYourEnemies3 nitõtọ. A ku Ayo Osu Titun. Happy New Month 💐 #GiveMeThisMountain #Yoruba https://t.co/YV98B0pjrv | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user @user Se e ti gba bayi? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀run ire ni fún ẹní ṣe ayée 're, oorun ire sì ni ẹ̀dá t'ó ṣe rere láyé ń sùn. #IkuOdaju #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó fi ọwọ́ tọ́’ni lọ́kàn gidigidi. A dára gan. Mo sọ pé, ẹ lọ wò ó. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
àgbà ti ń dé nìyẹn o wọ́n á dàgbà darúgbó lọ́lá olódùmarè | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
“@user: @user Akuko ko, Ole (Obun) pose, o ni, se'le tiya'a mo na nuu?”#owe #yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#OroRanpe : B'ọ̀wọ̀ fún bàbá àti ìyá è, ... #EdeYorubaDunLeti #yoruba #yorubaculture #lifestyleblogger #lifequotes #lifeisbeautiful #life #lifecoach #proverbs #quotes #quoteoftheday #videos #video @user Abuja, Nigeria https://t.co/6QqxOyhpSV | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Toò, ìbéèrè tí mo wa fẹ́ béèrè ni, táni Boko Haram? Tá ló mọ wọ́n kó wáá wí. A kú àyájọ́ ọjọ́ ìjọba àwa ara wa o. Ire o! #DemocracyDay2013 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Amin o, ire loju ojo nri o. Ayun lo, ayun bo lowo n yun enu """"""""""""""""@user: Ojúmọ́ ire o."""""""""""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Adúpẹ́, Ọlọ́run ṣeun #ATUNTE """"""""""""""""@user: Toò. Ọlọ́run ṣeun tó tún jí wa lọ́jọ́ òní o. Èmi dúpẹ́ mo yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀. #Oloru… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
nítorí náà ọ̀gá àgbàa ti gbaradì láti yànànáa ipa ayárabíàṣá fún ètò ẹ̀kọ́ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èyí ni àwọn àgbà fi ni """"""""àtẹ́lẹwọ́ ẹni kìí tan ni jẹ́"""""""", torípé àtẹ́lẹ́-ọwọ́ kì í parọ́, òtítọ́ pọnbele ní í sọ. #Atelewo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Kò tọ́pé o. Óku kí ẹ máà kọ Yorùbá jànkàn-jànkàn :)) | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àní mo rí obìrin ọlọ́pàá tó ń dá sọ̀ọ̀ ní Ọbáléndé nísẹ̀yín, ó jọ pé ó ti ya wèrè. 😮 @user | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Olúwa Kẹ́mi Sọ́lá; Olúwa kẹ́ mi sí ọlá - God pampered me into wealth #Oruko #Yoruba #Name @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
A-fún-irúgbìn l'ẹni t'ó gbin nǹkan. @user | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Alàgbà #FrederickFasehun, ẹ dákun àwa ń dúró kẹ́san ó ké lórí àwọn ọ̀bàyéjẹ́ tí ó fìyà oró jẹ obìrin méjì nì. #AjataOja | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Rárá miò ní gbà!, Ẹjọ̀ ọ́ẹ̀yin olùdarí àti olùṣe fíìmù Nàìjíríà, gbogbo nǹkan kò ló ní lati panilerin, ìmófo lèyí, ìmófo gbá à. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ọjọ́ wo ni à ń pè ní ọjọ́ Jàkúta? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ọbá mẹ́wàá ìgbà mẹ́wàá ló ni ilé-aiyé. Ẹnìkan ò lo ilé-aiyé gbó. Bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ló rí. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ nlẹ́ o ẹ sì kú ayọ̀ aṣọ tuntun | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
fìlà kérésì tí mo dé sórí ránmi létí fìlà ọdẹ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eniyan ti o so le nu o so apo Iya Ko. Da n saki fun ede ati asa yoruba. #TweetinYoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Lónìí tí í ṣe ọjọ́ Ajé tí ó ṣáájú nínú ọdún tuntun 2020, ire Ajé á ṣáájú ohun gbogbo tí mo bá dáwọlé. Lọ́dún yìí, n ó ṣe gbùdú n ó ṣe gbàdà bẹ́ja tútù ṣe ń ṣe níbú omi. Ẹ̀gà roro, ẹ̀gà ṣẹ̀ṣẹ̀. Ire Ajé tí mo pè á jẹ́ mi. Ẹ̀gà roro, ẹ̀gà ṣẹ̀ṣẹ̀. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn ará ẹbí wọn ma dá aṣọ jọ fún òkú náà, tí wọ́n ma kó sí inú ihò ilẹ̀ kí wọ́n tó tẹ́lẹ̀ òkú náà le ní orí. Ìgbàgbọ́ wọn ni wípé, wọ́n ń di ẹrú fún òkú náà lọ sí ọ̀run | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
7. Wọ́n á máa ní """"""""owó Àbú ni a fi ń ṣe Àbú lálejò"""""""", ǹjẹ́ o lè sọ àwọn tí a máa ń pè ní Àbú ní ilẹ̀ẹ káàárọ̀ o ò jí ire? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#Nigeria: èyí tí ó jẹ́ ìsúnkìi agbègbè Odò Ọya; (#Niger #area) lédèe Gẹ̀ẹ́sì. #IndependenceDay | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọmọ yorùbá ni mi n ò kí ń ṣe ọmọ àlè ọmọ ọkọ ni mi mi ò mọ ti ẹ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
sinemá àgbéléwò tí ó dára, tí àgbéyẹ̀wò rẹ̀ kò sí bàjẹ́ rárá. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
“@user: @user @user @user hi toyin...” Ọ̀rẹ́ mi òyìnbó báwo ni o :) #translation my friend how 're u? | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
seconds is not minute baba Seconds is Iseju aaya while minute is iseju #Yoruba is good to speak #CoronaVirusInNigeria #CoronavirusPandemic #YLagos #YLagos #YLagos #YLagos #YLagos #YLagos #YLagos #YLagos #YLagos #YLagos #YLagos #YLagos #YLagos #YLagos #YLagos #YLagos https://t.co/EJVh6lkFPa | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ló ti jẹ èèwọ̀, nǹkan ò bá wọ̀ fún wọn mọ́. Ọ̀pọ̀ ló ti pa ìṣèṣe ìdílée wọn tì. Ègún ìdílé bẹ̀rẹ̀ sí í jà fitafita bí ìjì, eku ò ké bí eku, ẹyẹ ò ké bí ẹyẹ, ọmọ ènìyàn ò f'ọhùn bí ènìyàn, ayé ti ṣá bálábálá. #OgunIleAye #EgunIdile #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Oro awon ara oke-oya yii wa su wa oo,bawo lese maa yinbon fun awon osise ilera bahun!!! | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìsẹ̀yín ni adájọ́ ń gba owó-ẹ̀yìn, a sì gbéjọ́ 'Sanjọ́ aláre fún 'Túnjí ẹlẹ́bi. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Atoto Arere..Arakunrin kan dana sun iyawo re lori esun wipe o n bi obinrin...arabinrin naa ti wa ni baku'bala bayi ni … | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: E gbayi yewo, ki e fi tiyin kun Eko Ede Yoruba http://t.co/82cGfXGXta @user @user @user @user… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìdílé wo ni ti ọọ̀ni okùnadé tó wàjà | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user @user Mo ki Oba tia, Olubadan tile Ibadan Oba Saliu Akanmu Adetunji Aje Ogunguniso kinni K'ade pe lori #TweetI… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
B'ó pẹ́ títí akálòlò á pe baba #Owe #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nínú gbogbo àwọn fíìmù tí ń ru ẹni sókè tí mo ti wò, eléyìí ló gbé igbá orókè.. . Ọ̀nà tí ó jọni lójú ni wọ́n fi darí rẹ̀ àwọn tí ó kópa níbẹ̀ sì ṣe iṣẹ́ takuntakun. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ó yẹ kí a sọ wípé, àwọn ọmọ Ẹ̀gbá Ọmọ Lúṣàbí ìlú Abẹ́òkúta ló ń kọ orin Sákárà jù lọ nílẹ̀ Yorùbá. #Sakara #Orin #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
In Yorùbá, oyin is honey while afárá oyin is honey comb #yoruba #yorubaword | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àyè kì í há adìyẹ kó mà lè dé ìdí àba rẹ̀. / A hen is never too busy to brood over its eggs. [We always make time for what is crucial to us.] #Yoruba #proverb | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
SEMANTICS IN YORÙBÁ / SẸ̀MÁŃTÌKÌ NÍ ÈDÈ YORÙBÁ Àwọn ọ̀rọ̀ tí ìrísí wọn jẹ́ ǹkan kan náà sugbon, tí ìtumọ̀ wọn yàtọ̀. Words with the same appearance but, different in meaning. Èrò - Thought Èrò - Crowd | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ múra síṣẹ́ o á yọrí sí rere | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
a gbádùn yín ganan ni lórí ètò náà o àwọn ìdáhùn yín jinlẹ̀ púpọ̀ yoòbá ẹnu yín mú bi abẹ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìtàn ìlú Máṣeé kọ́ wa pé kí a má wo ago aláago ṣiṣẹ́ àti pé kí a má ṣè kà, torí, ọ̀tafà sókè yídó borí lọ̀rọ̀ ayé. #Itanilumasee | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
L is for #listening Oluwa fún wa ni ,etí ìgbọ́. Amin🤲🏾 Hey Gistas mi ọ̀wọ́n, #itsmonday A kúu Monday o. Òní á sàn dede wa o. #ondo #yoruba #authenticwoman #newweeknewgoals https://t.co/2MtWBb4nJM | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""Ṣo rí to bá ṣẹ̀ṣẹ̀ kọlé, to bá lo jẹ́ mansion, wa á ni ilé mi l'eléyìí, AYÉRAYÉ ILÉ!"""""""" -Saidi Oṣùpá #yoruba #ijinleyoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Leyin aponle ... Abukun lokan.. #Yoruba https://t.co/qEvhA9HzLM | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ikilo pataki; imo toto ni'n bori arun m'ole, b'oye ti n bori oru. Toju ayike re lati dekun aisan. #TweetInYoruba https://t.co/vzbS00aQsb | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
aworan alaafin ilu oyoô oba lamidi adeyemi ti wa di akoda fun aare jonathan ori ade fi oyo sile lati pade ebele | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹrú kú nílé, wọ́n lọ sin ín s'óko. Ọmọ kú lóko, wọ́n lọ sin ín sílé. Bẹ́ẹ̀ nìbí ò jù 'bí, bí a ṣe bẹ́rú la ṣe bọ́mọ. #IworiOkanran #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Kò sí àṣírí kankan lorí Twitter o ọ̀rẹ́. Gbangba ni gbogbo ẹ̀ wà :)) | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Aki 'n gbale baba eni l'owo eni. Ewo awon ti a pe ki wan wa ba wa gbe po ni ile Yoruba. Arifin yi ma ti wa di kobo kobo o. Ti ogiri o ba lanu sile, alangba ole raaye wobe. Yoruba Ronu https://t.co/pXzUzIDCVr | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
10. Èwo ni ó tọ̀nà nínúu gbólóhùn méjèèjì : A. Àkàlàmàgbò kì í pa ọdún jẹ B. Àkànnàmọ̀gbò kì í pa ọdún jẹ #Ibeere #Yoruba #Owe | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
a óò wá àfòmọ́ tọ̀ọ́létọ̀ọ́lé bíi mélòó kan a ó jó o ní iná a ó gún un atọ̀ọ́lé yó máa fẹ̀kọ lò ó bíi àgúnmu | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo fi àsìkò yìí kí gbogbo ọmọ bíbí ìlú Ìsẹ́yìn kú ayẹyẹ tí Àjọ̀dún Ìsẹ́yìn Orò tí ọdún nìí, tí àṣekágbáa rẹ̀ yóò wáyé lọ́jọ́ kankàndínlógún oṣù Ọ̀wẹwẹ̀. Àṣèyí ṣẹ̀míì! Ìṣèṣe á gbè wá o! Àṣẹ! #Yoruba #Oyo #Isese | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eni ti ko ba ni'fe iya ti o bi i tokan-tokan, a padanu ibukun nla ni'le aye e @user does making my own Yoruba proverb count? #Naijaproud #wizkid #Nigeria #LoveYourMum #Yoruba #OmoBalogun #Iya #Respect #Love #Africa 💙😍 https://t.co/HQ5HcFwqcW | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àṣẹ ni ti oyin àlááfíà fún | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí a fi àyájọ́ ònìí fi ìfẹ́ bára wa ṣe, rántí wípé ìfọwọ́wẹwọ́ ni ọwọ́ fi ń mọ́. Ìfẹ́ la fi dálé ayé #Yoruba #OjoOlolufe #Nigeria | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo gbìyànjú kiní tí'án pè ní turban yìí fún ìgbà àkọ́kọ́ lónìí. Báwo ló ṣe rí? Ẹ má wo eyebag mi, I've been working overnights lately🤦🏿♀️ #iyayoruba https://t.co/g6p66GFXvE | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Lótìítọ́ àti lódodo, a ti kọjá àsìkò tí ó yẹ kí èèyàn kàn máa kọ ọ̀rọ̀ Yorùbá lásán láìfi àmì ohùn si. Ẹ jẹ́ a dẹ́kun àti máa ṣi àwọn Òǹkàwé lọ́nà. You can add the new feather """"""""Yorùbá Tonal Mark Activist"""""""" to my cap😊 #yorubarevolution #tonalsound #yorubarules #yoruba https://t.co/dtIxOPXauY | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
1. Ṣe ògbufọ̀ gbólóhùn inú àwòrán yìí: #Ibeere #Yoruba https://t.co/QhervtiSg7 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""@user Iwe ati wo ile iwe """"""""School of Nursing UITH, Ilorin"""""""" 2013/2014 ti ja de http://t.co/rdD2eALkyx http:/… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
koríko ti hù sóríi sàárè ìyá àgbà =► weed has grown on grandmas grave | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo kí olóṣèlú gbogbo. Àwọn ọlọ́wọ̀'gbálẹ̀, àwọn ẹlẹ́ṣin. Ẹ rọra kó owó wa jẹ o. """"""""Ó kù lódò"""""""" ni omi aṣiwèrè! | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
mbami e pòe seun púpò ire o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Lara awon ohun ti mo mu bo lati #akefestival ni iwe Ake ni Igba Ewe ti Wole Soyinka ko ti Akinwumi Isola tumo si ede Yoruba, mo n gbadun re | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìtàn tó dùn, eréṣíṣe àti àwọn òṣèrè kò dára | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
kábíèsí ọba ògo jọ̀wọ́ wá tamí lọ́re owó ọmọ àlááfíà àti àìkú baálẹ̀ ọrọ̀ káyé mi ó dára bo bá gbàgbọ́ pé á ṣẹ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user a o FI Lu bi awon oyinbo se Lu awon eru lojo woni ka si so si ewon gbere. Eyen nko? #TweetYoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àwọn àdánan nì kì í ṣe tilẹ̀ yìí rárá o amẹ́ la ti kóo wọlé | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
.@user Ole ponbele ni e, asiko e ti lo, alo rami rami lari, a ko ni ri abo eyin jegudujera to e FIXi apo yin laabe omugo Aaare Ebele | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
... Ọ̀nà Ìsokùn (Baba oyè Aláàfin), Àrẹ̀mọ̀ àti Alápìn-ín-ni òòṣà. #Yungba #EwiAlohun #Yoruba #Oyo | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
tó dúró gedegbe gbangba sáwọn ìyókù ni | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.