text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
Ṣẹ́ẹ́rẹ́, Èrèlé, Ẹrẹ́nà... Wàràwéré #oduntuntun2018 ń jó lọ, àmọ́ bí ọdún náà ṣe ń lọ, èmi àti ìwọ ò ní bá a lọ láṣẹ Ọba Òkè. Ẹ kú àmójúbà o! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀tàkìtì pọ́n'wọ́ lá, Ò b'omi 'ẹ́nu fẹ́'ná jó, Ò fìdìí aró ìyá ẹ̀ ṣeléérú, Balúbodè lọ́run, Oólabí ojigan lóògùn, Olówó Gbáròyèé, Ọláàlú o gbére owó kò mí, kí Ajé ó máa jẹ́ mi. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#iroyin, #yoruba, Odaran ni Matthew yii o ! O si tun fee dogbon gbe igbo wole fawon elewon… https://t.co/9J0UF1OuqC | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
otito oro ni se daadaa le wa bee sini awo pele ki ya | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọmọ ló ń sin òbí ẹ̀. Àmọ́ kò sí ẹni tí ò lè ra pósí, àna lè rà á. Ṣebí ènìkan ló ń sin ẹni tí ò lárá? @user | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ayọ̀ ọtí mímu tuntun rèé o.. . Ní gbogbo ìgbà tí o bá ti rí àwọn òșèré tí wón wọ wíìgì ọ̀ràn tuntune, kí o sẹ́ gẹ̀ẹ́ kan mú. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
E ma je ki a tori Ede ba eede je nitori bi a ba de lati Ede, eede la o pada si #OroAmoye | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user #IbadanCodeSprint oye ki aye wa fun awon onimo ede naa dara po month awon onimo ero lati mu ero rere yii wa si imuse | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Oruko mi ni Babatunde omo ilu Onigbongbo ni ipinle Eko, inumi dun pe mo je omo Yoruba #TweetInYoruba 🇳🇬 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
8. Ẹ̀gúsí ni a fi ṣe ògìrì, ẹ̀wà la fi ṣe gbẹ̀gìrì,_______ ni a fi ṣe ègbo. #Ibeere #Yoruba #Ounje | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àwọn kan ò mọ̀ pé ọ̀kan lára òòṣà ilẹ̀ wa ni ọyẹ́ atẹ́gùn tútù yẹn ganan ni | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
leyin odun mokandinlogun alaafin kede aare ona kakanfo tuntun leyin | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Epo parafín di góòlù, owó afẹ́fẹ́ ìdáná náà gbówó lórí, kò sì síná mànàmáná láti fi lo ẹ̀rọ ìdáná ìgbàlódé. Kí la wá ń wọ́ọ̀kì! #Nigeria | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
tí omi ẹni ò bá tí ì tóni í wẹ̀ á máa fi ńbọ́jú ni if the amount of water one has wont do for a bath one ought | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bí ẹ ò bá fẹ́ bẹ́ẹ̀, ẹ pe ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ 01-4408464 báyìí báyìí. #NoToSocialMediaBill @user @user https://t.co/Rw5ZZ7ITx3 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: I checked the meaning of 'Bí ọjọ́ ewúrẹ́ bá pé, a ní kò sí ohun tí alápatàá lè fi òun ṣe' on Itumo Mobile App, http://t.co/KIj… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Afi ki a bu omi suru mu. Ki a mura adura fun Aare @user nitori wipe ako mo boya iwaju loloko wan un wa wa lo, abi reversiii la wa! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
2.Òwe àlàyé ni """"""""pàṣán tí a fi na ìyáálé, ń bẹ lájà fún ìyàwó"""""""", Pa òwe alálàyé mìíràn. #ibeere #Yoruba #Owe | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
oluwa ma nje ri oluwa ma nje ri ohun ti yo gba igbagbo lowo mi o oluwa ma nje ri | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
mo ti sọ tẹ̀lé wípé àṣà ni orò bí wọ́n bá ń ṣe orò bíi ti ìkòròdú oríṣìíríṣìí ètùtù ni wọn yóò ṣe ìbọ yóò gba nǹkan ti rẹ̀ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user » Fún alábaraméjì, ìwádìí fi hàn pé orin kíkọ ń ṣ'ọmọnú àtìyá láǹfààní. ~ @user @user @user @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ti iro ba sa fun ogun odun! https://t.co/0P43ARNELe | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
kí a má fi ẹnití yóò ba àṣà jẹ́ fún wa sí ipò nítorí ìkan ńnú púpọ̀ nipò ọba tó fi agbára ìran hàn kò gbọdọ̀ bàjẹ́ o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ kú ojúmọ́ o. Ẹ kú ọjọ́ Ajẹ́ yìí. #ekaaro | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ewi ti o koni logbon to ye ki gbogbo obinrin ka ni""""""""""""""""@user: Ewì Ọmọge Ìwòyí http://t.co/KP5YILTRSh #blog #blogger … | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
name it segment abala sọọ́ lórúkọ we go into mathematics today what yorùbá word coined or derived can we use in place of formula a wọ inú ìṣirò ní òní orúkọ yorùbá ìṣẹ̀dá tàbí ìlò wo ni a lè lò dípò formula | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí ẹ dákun bá wa rí sí ọ̀rọ̀ ináa mànàmáná o, ìfàsẹ́hìn ló ń mú bá wa. @user #Nigeria | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí a tó ó ṣe iṣẹ́ kan tàbí òmíràn, ẹ jẹ́ kí bèrè lọ́wọ́ orí, kí Ajé ba bá wa gbé. Ire Ajé o! #IgbagboYorubaNipaAje | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Àwọn àgbàlagbà sọ̀rọ̀ wọ́n ní """"""""fìlà ò dùn bíi k'á mọ̀ ọ́ dé; ká mọ̀ ọ́ dé kò dùn bíi kó yẹ 'ni, kò dùn bíi k'á rówó rà á."""""""" Fìlàa Yorùbá ni ▪️ABETÍ-AJÁ (LÀBÀǸKÁDÀ), ▪️ÒRÌBÍ ▪️GỌ̀BÌ ▪️FÌLÀ ALÀGBÀÁ ▪️FÌLÀA KÁTÍKÒ ▪️FÌLÀA DÀRA ▪️FÌLÀ JOFỌLỌ Àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí ni o rí sí ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò yìí? @user #ireporterstv #BringBackOurGirls #BokoHaram http://t.co/1V4cK47362 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òwò làwọn ará ibí ń fi wá ṣe bí a ṣe ń gbójú sókè sí wọn fún ohun gbogbo. Wọn kò kọ̀ kí ẹ̀mí bọ́, àpò ara wọn ni wọ́n ń dù! #Iseselagba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí ni à ń fi aṣọ-ẹbí ṣe? #AsoEbi #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìtàn yìí jẹ́ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ ni ìgbà ogun abẹ́lé nàìjìrìà ni ọdún sì ọdún lójijì ni mo ké pé fáyà ohun tí | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Rírò ọpọlọ rẹ máa tó sú o | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user Ọbàkan = ọmọ bàbá kan (náà) Iyèkan = ọmọ ìyá kan (náà) | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Orin ìṣírí wọ̀nyí, orin èébú ni, orin ọlọ́pọlọ tí ń mú ìrẹ́pọ̀ wọ ìlú sì ni pẹ̀lú. #Gelede #Yoruba #IWD #IseseLagba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user ojumo ti mo nile kaaro oojiire. Ki onikaluku yara mo ise ni o...isè ni oogun ìsé | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ènìyàn ni Ọ̀rúnmìlà baba ifá, kí ó tó di ò-rì-ṣà. Ìwọ gan-an alára lè di òrìṣà, bí o bá tẹpá mọ́ṣẹ́ ọwọ́ ẹ, kí ọmọ aráyé fi mọ̀ ọ́ #orisa | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
eégún dánáfojurà alágbára eégún kan ní ọ̀gbómọ̀ṣọ́ tí ó fẹ́ràn láti ma wà nínú iná ni eégún yìí ìtàn wà wípé ojú ogun ni wọ́n ti gbe wá sílé bí eégún yìí bá jáde láàárọ̀ títí di ìrọ̀lẹ́ tó má fi wọlé kò gbọdọ̀ fi ojú kan eégún òmíràn | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wọ́n fi ìgò òfìfo ráńṣẹ́ padà sí Ọba, láti fi hàn wípé, àwọn fi ìfẹ́ gba ẹ̀bùn rẹ̀. Tìmí Ẹdẹ ráńṣẹ́ sí Àṣegbé láti bèrè wípé, kíni ṣíṣe, kíni àìṣe? Àṣegbé wí pé, kí Ẹdẹ fi àpò owó mẹ́wàá àti ewúrẹ́ mẹ́wàá ráńṣẹ́, kí wọ́n sì gbà láti ju ọwọ́ ogun | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
MINERALS IN ÈKÌTÌ AND WHERE THEY CAN BE FOUND/ ÀWỌN OHUN ÀLÙMỌ́Ọ́NÌ NÍ ÈKÌTÌ ÀTI IBI TÍ A TI LÈ RÍ WỌN (1): - Clay Kaolin - Ọyẹ́ Èkìtì - Cassiterite - Ìjẹrò Èkìtì - Columbite - Ìjẹrò Èkìtì - Tin Ore - Ìjẹrò Èkìtì - Aluminium Ore - Ọrin Èkìtì | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ǹjẹ́ o mọ̀ pé kìnìhún a máa pa tó ẹran ogún lọ́dún kan láginjù | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé yàtọ̀ sí àbàjà, gọ̀mbọ̀, kẹ́kẹ́, pélé tí ó jẹ́ ti ìran Yoòbá, ìlà jàmgbàdì/mànde àti túrè tí ó jẹ́ ìlà àwọn àtọ̀húnrìnwá aráa Mandingo àti Kemberi tí wọ́n darapọ̀ mọ́ wa ti fi ìgbà kan gbajúmọ̀ rí nílẹ̀ẹ wa? #Yoruba #IlaKiko | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user @user @user Mo tún taari iṣẹ́-ìjẹ́ mìíràn sí NB, torí ó ń dùn mí wípé wọn kò kà mí kún, nítorí wọn kò rí ẹ̀sùn náà bí ohun tí à ń gbé ní lánkẹ̀. Ohun tí kò tó bàbàrà ni @user kà á sí, ó sì ju bàbàrà lọ. #EtoOnibaara #consumerright #brandnegligence | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ejo mo bẹ àwọn honourable láti agbègbè wa ki wọn jọ ṣe ìdìbò totọ lórí restructuring | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà láti ọdún 1999 sí ọdún 2003, Dókítà Olufẹmi Okunrounmu, bàbá àti ìyá wọn bí wọn ní ọjọ kọkọnla, oṣ… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
tó kú yẹn níláti mọ nǹkankan ni wọ́n fi pa á | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Èmi ò mọ nípa Togo ṣùgọ́n mo gbọ́ pé wọ́n pọ̀ níbẹ̀. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ǹjẹ́ o mọ̀ pé #JingleOverLikeAMotor ni à ń pè ní jangoróvà epo mọ́tò ní #Naija? #DidYouKnowThat #NjeOMo | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user A si kii Iya omo ku ewu | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìdá ohunorí ayélujára ló wà lédèe gẹ̀ẹ́sì ìdá iléayé lẹni ìbílẹ̀ tàbí aláìgbọ́ gẹ̀ẹ́sì báyélujára bá jẹ́ fénìyàn gbogbo ní tòótọ́ ọ̀ràn ìsọditìbílẹ̀ pọn dandan gẹ́gẹ́ bí ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn àgbékalẹ̀ ti ní | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
fun ayeye yi ma a fun yin ni akosori timo feran ju lede yoruba timo ti mo lati igba ewe mi e ma bami kalo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ó n ṣe àfihàn àìkún ojú òṣùwọ̀n tó wà nínú abala eré yorùbá, 'Ajibade' tọkasí gbogbo ìjákulẹ́ tó wà nínú eré yòrùbá láì tijú | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ìnáwó Alẹ́ jẹ́ àṣà tó gbajúmọ̀ láàárín àwọn Yorùbá ìgbàlódé, títí di ìgbẹ̀hìn 99. Ayẹyẹ oríṣi bíi ìkómọ, ìsìnkú, ìṣílé, ìgbéyàwó abbl, ni wọ́n ma ń sún sí alẹ́, tí wọ́n sì ma ṣe títí di àfẹ̀mọ́jú | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
6. Ọ̀rọ̀~ìṣe àti ọ̀rọ̀~orúkọ ni a fi ṣẹ̀dáa àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí : Jẹ + iṣu = jẹṣu San + ara = sanra Ìwọ náà ṣẹ̀dáa ọ̀rọ̀ mìíràn. #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà tí eré kò bá ní ìdìtẹ̀ àti ìṣeré tó dára, yóò ní àwọn agbára ìràpadà, ṣùgbọ́n Olóye bàbá àgbà apá kejì kò ní. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
@user Ọmọ Ògùn! Ọjọ́ ọ̀tun ni kì í ṣe ọ̀tun ọjọ́. Ṣé ó yé? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àmọ́ ìyáa Tọ́ba ní'rọ́ pátápátá ni, pé nígbàtí òun àti @user ṣe ìwádìí, #Faisal àti #Olivia lọ́wọ́ sí ikúu Tọ́ba. #JusticeForTobaFalode | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìjọba Nàìjíríà, ojú yín dà! Ògo orílẹ̀ èdè yìí, kí ní dé tí a ò le è fà á lọ́wọ́ sókè! @user https://t.co/QmLZuRi5F5 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Tìkaraàmi = me with my fingers; me. (Èmi tìkaraàmi ni mo ṣe é = it is me, myself and I that did it) #InYoruba #LearnYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ọ-fẹ, bí a bá lo ọfẹ, a ó gbéra bí ìgbà tí àtẹ́gùn bá fẹ́ ìwé ni, a máa gbé 'ni fò. Láyé àtijọ́, àwọn gbéwiri máa ń lò ó. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn olórí Adó-Àkúrẹ́, fárígá, wọ́n ní wípé, Àkúrẹ́ gbọ́dọ̀ lọ singbà fún Benin, èyí wá mú rògbòdìyàn ṣẹlẹ̀ láàárín Àkúrẹ́ àti Adó-Àkúrẹ́ Benin ní iná tó ń jó wọn ní abẹ́ aṣọ lọ́wọ́, èyí tí kò fún wọn ní ìfọ̀kànbalẹ̀ láti pàṣẹ lórí àwọn ìlú tó wà ní abẹ́ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ojúmọ́ ire o. Ore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run Ọba kó máa bá gbogbo wa gbé o. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Látìgbà tí àyípadà dé bá bí a ti ṣe ń ṣiṣẹ́, tí àwọn ẹ̀rọ ńlá ńlá di ohun tí àwọn iléeṣẹ́ gbogbo ń lọ rọ́pò akitiyan ọmọ ènìyàn, tí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ lékan sí i ni ayé ti dàrú gùdùgùdù. N ò ní pé àwọn ìlọsíwájú wọ̀nyí kò dára, kódà dáadáa ò dáa tó o, àmọ́ ṣá o... | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user Ese gan, ati gbo. https://t.co/mGTRoY6HYs | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ará Èkó ò mọyì ará oko - (Those in Lagos; urban, no not the value of those in the farm; village, rural) #owe #yoruba #proverb | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ̀yin Ọmọ káàrò òjire o, àlọ́ tòní re o, kíni ìdáhún ti yín o. #folklore #alo #theyorubapeople #yoruba #blackpeople #cultur #ewi #asayorùbá #àsàyorùbá #àsà #traditionalart #oweyoruba #theyorubasocialarena… https://t.co/bJ2dSDsD5v | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bẹ́ẹ̀ ni, adìẹ àti ọmọ adìẹ ni, àmọ́ òkòkò ìyẹ̀lẹ̀ ni à ń pe ìyá, òròmọdìẹ làwọn ọmọ. https://t.co/5fJ1eEUEvD | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ooo e pa ahun #yoruba #yorubagbon | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
1-------- Kọ́nú n kọ́họ, Awo Èwí ńlé Aládòó, Ọ̀runmókùnkùnkanlẹ̀, Awo òde Ìjẹ̀sà. Alákàn ní ḿ bẹ lódò ní ń ṣe lákáǹláká peepeepee... #OseOtura #AyajoOjoObinrin #Ifa #Yoruba #IWD2018 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Asiko Olorun lo dara ju #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
emi ti ṣetán oo toò ta ló ṣetán láti ṣàtìlẹ́hìn fún àwọn agbábọ́ọ̀lù wa ní | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
alakowe o to ojo meta ojumo rere lo mo wa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Fíìmù òmùgọ̀ | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
eku oro ilu o oro di unmmmmmmmm oro pe si je o oro di unmmmmmmmm | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Má ṣe fìgbà kan kábàámọ̀ ohunkóhun tí ó bá ti dùn ọ́ nínú rí"""""""". - Amber Deckers #TranslatedQuotes #Quotes #AnyQuoteInYoruba #RandomQuotes # IyaYoruba https://t.co/45sR5PBKeB | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Tí a ti lá ò gba ti ìbílẹ̀ wa tí a ti di ìjílẹ̀ panpan àti ògbólògbó ń'nú rẹ̀ gbọ́ mọ́, ni a ò fi gbó láyé mọ́. #belubelu #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹṣin to síwájú ńkọ́? @user | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Bi ebi ban pa inu, Akasu bamba laa fi be A dia fun teyinbiwa tio san owo ipin lorun Mosan owo ipin lorun,mon… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìṣọwọ́ ṣeré tó mẹ́hẹ àti àwọn ǹkan kan tí kò mú ọpọlọ dání sí èmí ṣùgbọ́n ju gbogbo rẹ̀ lọ, mo gbádùn rẹ̀ b’óșe rí. Mo lè má tún un wò mọ́ láyé, àmọ́ ó dára ní ẹ̀ẹ̀kan tí mo wò ó yẹn. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
kí a ya jẹ́ kí erí orí wa ó fa epo mu ní kí a ye é forí fọ́ àgbọn fún olóòṣèlú kí a ye é ṣe ẹrúukú mọ́ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Sherwood ní wípé, ìbéèrè wọ̀nyí l'ó yẹ kí a dáhùn bí a bá ń sọ nípa ilẹ̀ Adúláwọ̀ tí a mọ̀ lónìí. #BlackHistoryMonthUK #OIANUK #Africa | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé àti ìkókóbìnrin àti ìkókókùnrin ni a máa ń lu etí fún láyé àtijọ́? Àwọn Yoòbá ka èyí sí àpẹẹrẹ pé ọmọ n… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eso ni elegede Pumpkin ni Oyinbo npee""""""""@user: @user kini elegede atipe kini Oyinbo n pe e?"""""""" | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ti omo eni ba daa kawi... Gomina Ajimobi n dara ni ilu Ibadan, ewo bi o ti n tun ona Challenge yii se | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Àṣẹ oo. Ìya wa ó mà ṣe'jọ́ mẹ́ta kan. Bóo ni nkan? | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nítorí ìfẹ́ tí ẹyẹlé ní sí olówó rẹ̀ làwọn àgbà fi ní “ẹyẹlé kì í bá onílé jẹ́; bá onílé mu kí ó di ọjọ́ ikú kò yẹ orí”. #BiEyekoSeDiEyele | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""@user, @user ile ejo †̥☺ gajulo ti da ejo gomina ipinle Ekiti ana Segun Oni’s da nu http://t.co/Pn0eey… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user a gbé aláwo ire ko'ni | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#yoruba Ọmọ Yoruba ní mí ooo https://t.co/mk02pcrhQm | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ní báyìí ẹ̀yin èèyàn rere ẹ jẹ́ ká máa bá ìtàn ògún lọ ẹ káàsán o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èkínní/ìkínní = first (èmi ni mo ṣe ipò èkínní - I made first place) • Ọ̀kan/kan = one (ọ̀kan lára wọn wá - one of them came) #InYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé gbólóhùn n nì """"""""yìgì"""""""" tí a máa ń lò rọ́pòo ìgbéyàwó, kì í ṣe èdè ilẹ̀ káàárọ̀-o-ò-jí-ire? Bẹ́ẹ̀ ni, àyálò láti inú èdè Haúsá ni yìgì/iyìgì. 💍 #Yoruba #Hausa | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Yoruba is Sweet. LWKM @user: Aare Orile ede Nijeria Dokita Goodluck Jonathan ko ni lakaye tabi ogbon ... h ... | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user @user @user @user Bi Latin se ri fun aguda ni Yoruba je fun awon Caribbean at Latin… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
OmoYoruba Nimi emajekin Sonu omo atata omo oduduwa #Oduduwa #yorubademon #yoruba #culture 👽🍯🌴🌵 https://t.co/yhEtUm2IzT | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
“@user: @user :Ase wa” bẹ́ẹ̀ làá rí | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
10. Ǹjẹ́ o lè sọ èrèdíi tí a fi pe foam ni fóòmù, bank ní báǹkì àti ọ̀rọ̀ bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ̀? #ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìrìn-kè-rin-dò. Ìrìn in òkè ìrìn in odò - journey of life; ups & downs, struggles. #InYoruba #learnyoruba http://t.co/DJPb3USL69 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí lẹ fẹ́ẹ́ ṣe ògbufọ̀ọ rẹ̀? @user #Traslation #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.