text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
Ni a fi ní láti máa se oúnjẹ dáadáa. Bí ìmọ̀ gbogbo, bí a bá ṣe ń s'oúnjẹ sí la ó ṣe mọ̀ ọ́ sè sí.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user #yoruba; ki lo nso?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Haaa Joonuu😱 ha Obinrin 🏃 #voiceover #yoruba https://t.co/IVj40KMJ5y
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Oooooo! Eyin na ku idodimu o. """"""""@user: Mo kí gbogbo èyàn wa l'ókè òkun àti lẹ́hìn odi gbogbo. Ẹkú àìgbàgbé ...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user ... O kú ìnáwó ọjọ́ o, Basiratù Àbẹ̀kẹ́ o. Basiratù Àbẹ̀kẹ́ ṣ'òkú màmá rẹ̀, ó lárinrin... Ọmọ Sàlàwẹ̀, Àbẹ̀kẹ́ wẹ̀ lódò ó ń yánwọ́ ọṣẹ 🎶 Tóò, èyí tí Ọlátúnjí kọ ni mo mọ̀ tẹ́lẹ̀, ẹ̀yin lẹ jẹ́ n mọ ti Eégúnmògají 👍🏿. Kí ikú dẹlẹ̀ fún wọn!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ta ni ò sàì ní wí pé à‎​jẹ́ àná ló pomo jẹ
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: 11. Ikú kì í pa ẹtà lójú 'ran. Kí ni ẹtà? #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ase o""""""""@user: A kú ọrọ̀ Ajé àt'òórọ̀ o. Á yẹ wá kalẹ́ o.""""""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àfọ̀njá ló fa sábàbí onírúurú ogun jagun kẹ́rù kẹ́rú ọlọ́dun pípẹ́ ìran Yoòbá. #AareOnaKakanfo #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìdílé eléégún ò ru agọ̀ mọ́ àwọn oníṣàngó ti pa oṣée ṣàngó tì ìdílé aláwo ti da ifáá wọn nù a kò ṣe orò ìdílé tó yẹ ká máa ṣe mọ́ a ò ṣẹ̀tọ́ fún alálẹ̀ mọ́ alálẹ̀ náà ò ṣẹ̀tọ́ fún wa mọ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orí wò ibi rere gbé mi dé ẹsẹ̀ wo ibi ire sìn mí yà nítorí orí ni ẹjá fi ń la ibú jà nítorí orí ni àkèré fi ń wẹ̀ ni odò oríì mi àpésìn
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user @user @user @user @user @user @user @user Jọ̀wọ́ gbìyànjú láti fi àmì sí ohun tí o ń kọ nítorí pé ọkọ yàtò sí ọkọ̀, ọ́ sì yàtò sí ọkọ́. ẹ̀rín kẹẹ́kẹ̀! #TweetinYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#iroyin, #yoruba, Iranse okunkun ni Makarfi ati Fayose je ninu egbe PDP - Kashamu: Seneto… https://t.co/yxUH88d1kO
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
nise ni a o tun maa jeri won wipe awon ni won daa ju lagbaye mtcheeew
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wó̩n kàn s̩e àtòpò̩ ò̩kan-ò-jò̩kan ẹ̀fẹ̀, àwọn àwòrán apanilérìn-in tó ti wà lórí ìtàkùn abánidó̩rè̩é̩ lásán ni. Wọ́n tó gbogbo rẹ papọ̀ wọn sì pè é ní eré tiwọn. Tí ó bá jẹ́ ẹni tó wà lórí ìtàkùn abánidó̩rè̩é̩ ni, wà á ti ṣe àkíyèsí ọ̀pọ̀lọpọ̀ won bẹ́ẹ̀ni kò sì dájú pé wo̩n yóò pa ọ́ lé̩...
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ètò ìlera t'ó yè kooro fún aboyun #2030Now #2030Naija #MDGs #Nigeria @user @user http://t.co/bit4r7ZjM5
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bringing back the classics a mú àwọn orin ayébáyé padà wàá káyọ̀dé fáṣọ̀lá bí pẹ́pẹ́yẹ bá jòkúta what memory does the song bring back to you kíni orin yìí múu yín rántí
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ewúro l'àgbà igi o, ewúro làgbà igi x2 Gbogbo igi ẹ bọ̀wọ̀ f'éwúro Ewúro l'àgbà igi.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
a dúpẹ́ o a ń wojú ẹ̀ dé nkan bí ago mẹ́jọ ó yẹ kó ti kásẹ̀ ńlẹ̀ láago méjìlá ẹ ẹ̀ yáa kọrí sí ibiṣẹ́
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré tó tayọ. . . . Eré yii je eré tí ó tayọ lati ọwọ́o nollywood. Ìyà lénu ló jẹ́ fún mi bí ìpele dídára eré yii ṣe jẹ́. Sinimá Naijiria n ga si nítootọ́. Isẹ́ tó dára, a ní lò àtẹ̀lé rẹ.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Òwe ní, """"""""eré là ń fi ọmọ ayò ṣe"""""""". Èso igi arère ni à ń pè ní ọmọ ayò tí a fi ń ta eré ayò ọlọ́pọ́n. #Yoruba https://t.co/Z1…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Yorùbá: A tonal language in which difference in tone brings difference in meaning. Ìgbà (Time) Igbá (Calabash) Igba (200)…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: OPE NI FUN OLOHUN..SE ALAAFIA NI? @user: Ẹkáàárọ̀ o.. ẹ̀yin ará mi. Ṣé dáadáa la jí o?
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
njẹ́ èmi alákọ̀wé mo ti dami síwájú ó ku kí n máa tẹlẹ̀ tútù
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹkú iṣẹ́ #SaveFunmi o. Ọlọ́run á san yín lẹ́san ire!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: A kú ọdún Àjíǹde o, ẹ káàbọ̀ sí ọ̀sẹ̀ tuntun! Our Yorùbá adage for the week:""""""""""""""""Ọjọ́ a gùn kọ́ là ń kan'run"""""""""""""""" Translation: """"""""""""""""…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ̀wẹ̀, Manchester ń ti rẹ̀, di ìlú olówó látàríi òwò òwú tí ẹrú gbìn ní America àti Brasil. #OsuItanAduNiUnitedKindgom #OIANUK
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹgbẹgbẹ̀rún ló ti ka gbogbo ìwé, tó sì ti kiri títí bàtàa rẹ̀ fi lá, síbẹ̀ kò ríṣẹ́"""""""" #OhunOdoNigeriaKan
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹni t'ó bá mu ọmú dáadáa fún ọdún méjì gbáko ò ní mọ aàrùn. Àrùn ọkàn àti ìtọ̀ dídùn yóò jìnà sí onítọ̀hún lọ́jọ́ iwájú. #WBW #efomoloyan
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ pé igi igbó kan wà tí ọ̀gbìn ò le è hù sí abẹ́ẹ rẹ̀? Àti pé pípa ni igi nì yóò pa ẹyẹkẹ́yẹ t'ó bá fò sún mọ́ ọ jù? #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
happy new year ki odun ayabo fun wa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Aare America f'ehonu han si awon mokanlelaadota ninu Ile igbimo asofin ilu America leyin to won ko lati gbegi le #obamacare #TweetinYoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọwọ́ọ wa yóò ma jí sówó, ajé á máa bá wa gbé láti ònìí ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ Ajé lọ, títí láí #ase #yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
aworan alakori ma ni osere charly boyi ni se lo hun ba iyawo aare jonathan tage ni gban gba iyawo aare tura sile
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn ìpele kọ̀ọ̀kan nínú eré àgbéléwò yìí tọ́ni lọ́ọ́kàn. Ìwọ náà wòó.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ohun tí à ń wá lọ sí ṣókótó wà lápòo ṣòkòtòo wa ọ̀kanòjọ̀kan igi ń bẹ nílẹ̀ yìí tí yó fọ ẹnu mọ̀ ṣáká
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àpẹẹrẹ tí òṣèré tí kò ní ìbámu sí ipa nínú fíìmù yìí ni Tọ́pẹ́ Tedela. Nínú ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí mai-suya ọlọ́kọ̀ọ́kọ̀ọ́-ọ̀wọ́-ọ̀wọ́, ó ti sàn jù ó sì sọ̀rọ̀ dáradára.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
to ki oluwa ma se wa loni ise ka owo filogba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ará Èkó ò mọyì ará oko """" - the Lagos folks; urban no not the value of the farm dwellers; rural ► http://t.co/JzIV9Obs5L #Blogs
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ago mi si kun akunwosile lorukoJesu. Amin! #YorubasOfSocialMedia #TweetinYoruba https://t.co/NALZZhAg7t
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
We #Yoruba are omoluabi meaning Omo ti Oluwa bi.... https://t.co/WtlkgWjdhX
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ilu ibadan ni ipinle oyo orilede nijiria mo feran ilu ibadan pupo ilu awa akoni
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Abala ke̟rìnlá. E̟nì kò̟ò̟kan ló ní è̟tó̟ láti wá ààbò àti láti je̟ àǹfààní ààbò yìí ní orílè̟-èdè mìíràn nígbà tí a bá ń s̟e inúnibíni sí i. 1/2
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
MO ti ká ìwé náà, mo sì rọ wípé èrè náà dára pẹlu iṣẹ́ tó lágbára nípasẹ̀ àwọn Òṣeré pàtàkì. Ó jé ọkàn lára àwọn ère tó dára tí mo ti wò nínú ọdún yìí pẹlu ìròyìn àtijó tó wepọ mọ ìtàn náà.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Èèmọ̀ pẹlẹbẹ rèé o, àfi bíi òkú àkúfà, ẹbí, ọ̀rẹ́ àti àwọn ẹniẹlẹ́ni agbóòkú #MIC ló tún forí kóo. Ó di gbére #RIP #AssociatedAirlineCrash
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ará ẹwá wo yẹ̀yẹ́ àwọn aṣòfin ilé igbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Rivers ní Yorùbá http://t.co/PXMnbExO7h #yoruba @user @user…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
won ro wipe a gö bi ti won ni mùmú ni wọ́n ń pè wá
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Adú; John Baptist Dusable bá India ṣe òwò, ọkọ̀ orí omi ni John fi n kó ọjà. Ichicargo l'ó di Chicago. Adú t'ó kọ́kọ́ dé etí omi. #BHM
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
frederick fasehun olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ opc jáde láyé iroyin sọ pe alagba faṣeun jade laye ni owurọ ọjọ abamẹta ni ileewosan nla fasiti ipinlẹ eko lasuth ni ikẹja
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àwọn ẹ̀gbá ka ìtakété sókè ìkòròdú sí ohun àbùkù sí ẹ̀gbá ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún ẹ̀gbá rán ọmọ ogun ẹgbẹ̀fà sí ìkòròdú láti pa ìlú náà run àwọn ọmọ ogun ẹ̀gbá rọ̀gbà yí ìkòròdú ká nígbà tí ọ̀rọ̀ yìí dé etí ìgbọ́ ìjọba britain wéré ni wọ́n
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí a bá wòó, à á ri i pé ó jọ ọpọlọ, ẹ̀yin ẹ lọ wo àwòrán ọpọlọ kí ẹ fi wé àsálà. http://t.co/JvQRyAqCjz #Yoruba #asala
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ṣé mo jọ Sányẹ̀rì ni? Ọ̀rọ̀ àwàdà kọ́ l'ọ̀rọ̀ #BBNaija yìí o. Gẹ́gẹ́ bí CDQ ti ṣe kọrin, ó ní """"""""""""""""k'ólóṣó jọ sínú ilé bíi ti..."""""""""""""""" Kò sì purọ́.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bóo wá ni a ṣe ń dá irun ará inú aàfin mọ̀ a ó sọ̀ yẹ lọ́la ẹ ẹ ọjọ́ ire ire o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹni tí kò mọ bí ẹgbẹ́ rẹ̀ ṣe là á sá àsákú whoever unduly bothers about his or her peers relative successes will
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Àyájọ́ òní ní 1864 ni Sámúẹ́lì Àjàyí Crowther di Bíṣọ̀ọ̀bù àkọ́kọ́ nílẹ̀ Adúláwọ̀. #Yoruba #iseleana https://t.co/0xk91hPBsb
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn kan ò sanwó (bí ìyá Fẹlá), wọ́n bára wọn látimọ́lé, síbẹ̀ wọn ò bojú wẹ̀hìn fífẹ̀hónú wọn hàn síjọba. #IseleAtijo #Yoruba #Kirikiri
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
WHO DO WE EULOGIZE THIS WAY: Ọmọ gb'élé gbé ìgbẹ́, ọmọ gbé ní oko, gbé ní ijù - Iwájú jí ẹ̀ṣọ́ ti ń gba ọ̀tá. Ẹ̀ṣọ́ kan kìí gba ọta láti ẹ̀yìn - Ọmọ arógun jó, ọmọ arógun yọ̀ -Ọmọ agbogun ṣ'owó ṣe Ọmọ aṣáájú ogun, máà kẹ́yìn ogun?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Èwà? @user: Ó bí igba ọmọ, ó tó tìróò fún wọn o? Kí ni o? #tweetYoruba @user @user @user @user…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user — itakun ile ki ni igbin ni ara, Awolule ki í pa olongbo ako..... Osu titu koni ni wa lara o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ̀kọ àsìkò sàn ju iyán ewú lọ. / Fresh pap is better than stale pounded yam. [Be perceptive to choose wisely.] #Yoruba #proverb
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user mo ma n gbadun bi e se ma n se ati bi e se ma n gbe asa ileewa l'aruge. Eyin la o maa ba, awa le o maa r…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""@user @user Ẹ kú ìrìn. Adúpẹ pé ẹ b'àlẹ̀ layo. Ẹlẹ́dàá ṣeun
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré tó tayo láti orílẹ̀ ède nàíjíríà. . Inú mi dùn gidi láti bá a pàdé. Mo gbádùn eré yìí láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin. Mò ń retí apá kejì.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
àwọn ọlópàá tí wọ́n ndáàbò bo àwọn èrò ìrọwọ́rọsẹ̀ ni gbogbo nkan nlọ wọ́n kú iṣẹ́ o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ó jé ìjánikulẹ̀ ìwé tórewà
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
yíyẹ ní í yẹyẹlé rírọ̀ ní í rọ àdàbà lọ́rùn pẹ̀tẹ́pùtù ní í ṣadìẹ àba yíyẹ ni yóò máa yẹ mí rírọ̀ ni yóò máa rọ̀ mí lọ́rùn ọgbọ́n kò ní pin mọ́ mi nínú iyèè mi yóò máa là wàà ọ̀nààn mi kò ní nà mí iléè mi ò ní lé mi ilẹ̀ ọ̀gẹ́rẹ́ yóò máa rú fún mi tẹ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
puro n niyi ete ni muwa afi fila peerin ojo kan lo niyi mo proverbs
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Bíbí ire kò ṣé fowó rà. Ẹkú ọjọ́ ìbí o. Ẹ̀mí á ṣọ̀pọ̀ rẹ̀ láíyé. Ọdọdún lá nrí ọmọ obì lórí àtẹ. Ire lẹ́ ó máa rí títí aiyé!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user @user @user Karin kapo ma n dani duro ni opolopo Igba baba.... ko kin yeni…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìwọ lónìí ìwọ lánàá bí ẹkún apọkọjẹ
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Nítorí yíyẹ ní í yẹyẹlé, dandan ni yóò yẹ mí kalẹ́, k'ára ó rọ̀ mí dẹ̀dẹ̀, ṣẹ̀ṣẹ̀, bí ó ṣe rọ àdàbà lọ́rùn. #Iwure #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àgbálùmọ́ dùn ọmọ ọba ló fẹ́ mu ú
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bìlísì yóò wà nínú ìdè fún ọgbọ́n ọjọ́, lẹ́yìn ọgbọ́n ọjọ́ wá ńkọ́? Bìlísì á gba òmìnira. #OroSunnunkun #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user ...ojumo re...oni a san wa oooo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user ojumo ire lo mo wa loni. Ope n la ni fun Eledumare.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òròmọadìyẹ ńbá àṣá ṣeré, ó rò pé ẹyẹ oko lásán ni. / The chick gullibly plays with the hawk believing it to be an ordinary bird. [Naivety can be risky, if not fatally costly.] #Yoruba #proverb
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré tó dára. . Àmọ́ ó sì le dára sí. Sùgbón gégé bí eré àkọ́kọ́ nínú àwọn eré sáyẹnsì, ó dára púpọ̀. Àwọn kókó eré náà yeni bésìni eré náà parí dáradára.. . Nítòótọ́, mi ò mọ òhun tí mo lè retí àmó, níìṣe ni ma màá tẹ̀síwájú láti wọ irú àwọn eré yìí sí.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Àyájọ́ ònìí, ọjọ́ kẹ́ta 1976, láyé Múrítàlá, a dá ìpínlẹ̀ Ògùn. Ó pé ogójì ọdún tí a dáa. Ọmọ #Ogun mo kíi yín! #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user bẹ́ẹ̀ ni, ẹ kú làákàyè
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""@user @user @user Egbe Oluburela ki Gomina Fashola lo ri iku Pa Fashola, Ajalu nla leyi http://…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kẹ̀tẹ̀ ni à ń pe irúu màálù báyìí tí ò ní iké lẹ́yìn nílẹ̀ẹ́ yoòbá
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ó wu ẹrú kó ṣe bí ọmọ orúkọ rẹ ni kò jẹ́. / A slave would love to act like a free-born but his name would not let him.…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Àwọn aiyé gbé àpótí jókòó lòrí ọ̀rọ̀ Bùhárí - Fẹ́mi Adéṣínà ló sọ bẹ́ẹ̀.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user mo ti ntele yin bayii inu mi yoo dun ti e ba tele mi pada
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bótilẹ̀jẹ́pé kò sí ǹkan tó tèni lọ́rùn, lára eré Àyìnlá, eré náà dára púpọ̀ àti pé ṣíṣe latifu tó kú díẹ̀ káà tó, ìyẹn kò sọ wípé eré náà kò dára.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ti ìpinnu dáradára ṣùgbọ́n ìgbìyànjú má gbowó láti gbé olùwò náà.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ọmọ #Nigeria ṣ'álàáfíà ni!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí wá ni ẹtà ní Gẹ̀ẹ́sì? #Eta
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Gbígbé lọ́ra, ìṣeré ńlá àti pé ó ní àwọn bíba díẹ̀ nínú, ṣùgbọ́n ìparí kò ní ìdáríjì.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
fiayokemi_oluwa in Ajegunle. 👉 Yorùbátv ẸGBẸ ỌMỌ OLÚWA BÍ GBOGBO ÀGBÁYÉ Ojú òpó ìkànsíraẹni 🇳🇬🇹🇬🇧🇯🇧🇷🇨🇴🇨🇺🇬🇭🇨🇮______________________________□ Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba #yorubatv #yorubaweddings #ebi #asoebi… https://t.co/N3gtvsqsxi
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wọ́n lérò pé àwọn apániláyà #terrorist ló fipá gba ọkọ̀ òfuurufú #MH370 ọ̀hún. @user @user
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
iyawo nnamdi kanu nikan lo le sọ pato ibi ti ọkọ rẹ wa lai muhammed
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kí Olódùmarè sàánú gbogbo wọn. #DanaAir
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
èwo nínú àwọn kòkòrò wọ̀nyí ní í máa ń mú oorun kun ni lẹ́yìn tí ó bá ti ta ni a irù b taniṣánkọ d gbòingbòin
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kò sí bí ìgbẹ́ ṣe lè ta kókó tó, erin óò kọjá. #Owe #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
1. Òkè Àgọ́ Òwu, Òkè Olúmọ, Òkè Ọnà. Àdó Èkìtì, Ìyìn Èkìtì, _______ Ìjẹ̀bú Òde, Ìjẹ̀bú Ìliṣàn, Ìjẹ̀bú Igbó. #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kí a ṣiṣẹ́ ká lówó lọ́wọ́
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
aláṣàkẹ́ fakọ yọ àṣàkẹ́ ṣe bẹbẹ obìnrin bí ọkùnrin arẹwà ọmọ́dayọ̀ gba ọ̀pọ̀ ìbéèrè òní
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó yẹ kẹ́yin ojú ó mọ́ ni, ibi funfun gbọ́dọ̀ wà bẹ́ẹ̀, bákan náà ni dúdú ojú gbọ́dọ̀ dú síbẹ̀ ni. #Glaucoma
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
aláìníṣẹ́ obìrin ò yẹni obìnrin tí ò níṣẹ́ ara rẹ̀ ló tàn jẹ a kun ojú a kun ẹnu a ṣàgbèrè lọ́nà ọjà
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train