text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
ó ku wákàtí mẹ́fà kí ọdún kásẹ̀ ńlẹ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Idakẹjẹ mi fẹrẹ ju idà eyikeyi lọ My silence is shaper than any sword #Yoruba #Oduduwa #Ifa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ANUOLUWAPOSI × Yoruba The mercies of God are ever increasing. #Anuoluwaposi #Yoruba #MARDLife #AfricanNames #NigerianNames #NamesAndMeaning #NameAndMeaning #MeaningOfNames #Meaning #Mercy #Increase #Anu https://t.co/W2iTSyj2JV
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
òtito oro eku abo eku atijo """"""""""""""""@user: Agbo to tadi meyin,agbara lo lo muwa,eku ati o""""""""""""""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọ̀rọ̀ bíi ó dọ́tí bíi ẹlẹ́dẹ̀ ò jìnà sẹ́nu wọn onídọ̀tí ni wọ́n ńlo ọ̀rọ̀ yìí fún torípé ọ̀bùn ẹranko ni ìmàdó ̀bá
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
oluwa oshe to jen ri ojo eni module lowo re olorun make she iyanu ninu aye like
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
fòyà. Nítorí akọni àti akíkanjú ọkùnrin ni òhun fúnra rẹ̀ jẹ́. Àwọn ọmọ ogun bá fi ipá wọ inú ààfin. Aláàfin Káràán dúró bá wọn taá tán. Ó bẹ̀rẹ̀ si ní fi ọfà jà, tí ó ń yin ọfà pa àwọn ọlọ́tẹ̀ náà. Ó ta ọfà títí, ọwọ́ rẹ̀ wú. Nígbà tí ìjà náà gbomi, ó gun
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Fíìmù tó níyì. . . òṣèré pàtàkì rẹ jọmílójú,orin tí wọn yàn kún ojú àmì, ẹdá rẹ dára lọpọlọpọ.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user Ojúmọ́ ire o. Ẹ kú àmójúbà oṣù tuntun yìí.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bí a ṣe ń ṣe àyèwò fún jẹjẹrẹ ọyàn
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré alágbára tí agbọn ìtàn tí a ti gbàgbé . Èyí kìí ṣe fún àwọn tí kò ní àyà.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Owú = jealousy • Jowú; jẹ-owú = to be jealous {ẹ̀gbọ́n jowú àbúrò - the elder is jealous of the younger} #InYoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ́kọ́ tí ó dára, ṣíṣe rẹ kò dára
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user @user @user Hẹ̀n Àwọn méjì tí ẹ fimí wé jùmí lọ rẹpẹtẹ o! Àmọ́ ẹṣé ẹkú ìgbéga. Ọlọ́run a gbé ẹ̀yin náà ga o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Headdress (Egungun or Gelede), Yoruba, 1901 https://t.co/3AwKl6G47O #yoruba #museumarchive https://t.co/umjp7PVHMW
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀rọ̀ #BokoHaram yìí mà wá dójú ẹ̀ o.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nítorí owó àpèkánukò, àwọn onígẹdú ti fi ọkọ̀ agbégilódò kó gbogbo igi igbó tà tán. Ogunlọ́gọ̀ igi gẹdú oníyebíye ti di títa sí òkè òkun. Àwọn tí kò sì bá èbúté lọ sí ìlú òyìnbó, wà ní ìsò pátákò tí àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà àtagbẹ́gilére ń fi wọ́n dárà tí ó wù wọ́n.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
oúnjẹ dàrá pọ́ amalá ati ewedú pẹlu gbẹgiri lòri fẹ́rẹ́fẹ ara mi balẹ̀ lẹyin ìrẹ́si ati àárọ̀ à fí ìpanu
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wọn kò buyì kun tó.. . . . Àwọn òṣèré dáradára. Ipa ìtàn dáradára. Ó rí gẹ́gẹ́ bí àwọn nkan ṣe rí ní Ilẹ̀ aláwọ̀ dúdú.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ìjákulẹ̀ ńlá lèyí o.. . Gbogbo àwọn ibi tí wọ́n ti ń jà níbẹ̀ ló dà bíi àwàdà Kẹríkẹrì.. . Àwọn idán sinimá Kankan kò sí níbè rárá.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
láyé ọba adémọ́lá ii aláké ẹ̀gbá ni kirikiri ìyá fẹlá pẹ̀lú àtìlẹ́hìn ẹgbẹ́ obìnrin awu wáyé
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Pé Nọ́líwuùdù yóò lè ṣe sinimá gidi kò dájú rárá.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Àní mo gbé'yìn f'Ọlọ́run. Ọba tó jẹ́ pé bí kìí ṣe tiẹ̀ ni, bí akálòò fẹ́ kéwì, bí arọ fẹ́ súre l'ọ̀rọ̀ wa ò bá rí. #ekaaro
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
gbogbo èrò ìkà láyée wa kì yóò bọ́si òkìkí wa yóó túbọ̀ máa tàn káyé
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
O jẹ́ mọ̀ wípé kò sóhun tuntun lábẹ́ ọ̀run! Ohun tí ó ti wà tẹ́lẹ̀ ni a ti mú nǹkan òde òní. Àfikún mọ́ nǹkan tẹ́lẹ̀ ló di tuntun.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Se lori oro #OsunDecides2018 #OsunElection yi abi nkan mi wa ni be ni. @user eso fun Unku @user ki wan ye pe maaalu ni buoda nitori at je suya! https://t.co/NcyFltRf3C
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀, Ológìní ní """"""""ọ̀rẹ́, ọ̀la ni ìkómọjáde kò sì sẹ́ran tá á fi ṣe é, mo wá ní kín n wí fún ọ... #itan #yoruba #oremeji
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user E ku ojumo. Ki Oluwa so awa ti awa ni irin ajo, ka bale layo.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
eran iya osogbo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Èjiogbè lóní kí ó gbè wá, káyé ó yẹ wá @user @user @user #Ifa
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
»» 641 ni Arab gba ìlú Kemet [Egypt]. 648 ni a gba Tripoli, 669 ni Tunisia, 680 ni a gba Morocco. #Atunko #nigbatiwonde
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
...Ìbọn àtijọ́. Àwọn ọmọ ogun Britain fẹ́ ẹ̀ tó ẹgbẹ̀rún kan. Wọ́n sì gbé ẹ̀rọ ìbọn pẹ̀lú. Ní ìgbà tí ọwọ́ àwọn ọmọ ogun Britain ju ti Ìjẹ̀bú lọ, Àwùjalẹ̀ gbà wípé Britain ti ṣẹ́gun Ìjẹ̀bú. A tún lè pèé ní """"""""Ogun Ìmàgbọn""""""""
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Irú yádi fíìmù. Mo kórìrá gbogbo dídágbé mi nìkan kejì tì o. Ìdọ̀tí ńlá!
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
oníṣàǹgó tí wọ́n bá dájọ́ ikú fún ẹni kejì sí ìyá naṣọ ni ó ní iṣẹ́ láti fi ojú ọmọba sí ọ̀nà bí w tí ń bọ ṣàǹgó obìnrin kẹfà àti ìkéje àwọn ni ẹni tó sún mọ́ ọmọba tó dàgbà jù bíi ìyá tí àṣẹ àti dárí apá kan ìlú wà lọ́wọ́ rẹ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Àìní ìforítì àparò ló sọ ọ́ di aláṣọ pípọ́n. / Patridge's lack of perseverance is what gave it its dirty garb. [Persev…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọ̀rọ̀ kànkà ọlọ́run ṣáà má jẹ́ wọ́n múná lọ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
6. Ní sáà Aláàfin Ọ̀yọ́ wo ni Ìbàdàn kúrò lábẹ́ ìṣàkóso Ọ̀yọ́, tí Baálẹ̀ Ìbàdàn sì di ọba Ìbàdàn? A) Ṣàngó B) Ṣiyanbọ́lá Ọládìgbòlú D) Làmídì Adéyẹmí #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àfòmọ́ ìbẹ̀rẹ̀ 'À' ni a hun pọ̀ mọ́ LỌ tí a fi ṣ'ẹ̀dá ÀLỌ. Ṣ'ẹ̀dá ọ̀rọ̀ mìíràn pẹ̀lú àfòmọ́ ìbẹ̀rẹ̀ À. #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré yìí mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìrètí dání ṣùgbọ́n ó padà di oun tí ó ń múnú bíni púpọ̀.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
fẹ́rẹ̀ dàbi sinimá méjì tí ó yàtọ̀. Ìtàn náà nílò ìtúmọ̀ tó súnmọ́ sí ti àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí n ṣẹlẹ̀.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
♫ A óò para wa láyò. Olele!!! ♪ Ó yá k'á para wa láyò, èmi ni ọ̀ta, ẹ̀yin ni òpe. https://t.co/TalvKnmqcy #Yoruba https://t.co/AEgTPV2AOE
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo f'ìrù yọ̀ yín o, ẹ̀yin obìnrin. Ẹ̀yin lẹ lòní, mo kí i yín fún ìsààmìn ayẹyẹ àyájọ́ obìnin. #IWD2016
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
♫..Ọṣé, oṣé o, oṣé o, kẹ́ wá máa lọ ♫ :) #ACN2013 #TeamEagles
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nǹkan ẹ̀rọ̀ mìíràn #idahun #Ibeere #YorubaQnA ► Orí, iyẹ̀pẹ̀, atare, oyin, omi; ìtọ̀, itọ́.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré tó dára gan ni o sì kọ́ ní lọ́gbọ́n
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
10. #Parioweyii Ẹni tí a bẹ̀ tí ò dárí ji 'ni... #Ibeere #Yoruba #learnyoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ó tì o ẹnu yìí yàtọ̀ sí ti tẹ́lẹ̀ o àbí ojú ń dùn mí ni
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
8. Afọwọ́lába-ajé-tete ⏩ ẹni gíga Ọ̀yọkùn-bẹ̀nbẹ̀ ⏩ ẹni tí ó yọkùn Abó-ìrókò-láti-fi-lówó ⏩ _____ #Ibeere #Yoruba #Oruko #Inagije
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ogun tí ó gbajúmọ̀ bí ìṣáná ẹlẹ́ta lágbàńlá ayé wo ni àwọn yoòbá pè ní ogun dìfọ́ọ̀sì
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user O ṣì í! Àìṣe dédé ń bẹ nínú àgbékalẹ̀-ẹ òwe náà, ìyẹn ní kíkọ. Y'ọ̀bẹ tì í ni ó tọ̀nà kì í ṣe 'yọ bẹ tí', ṣ'ómi sì ni, kì í ṣe 'ṣó mi' . #LearnYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìbàlé ► hymen tẹ́lẹ̀ ọmọbìrin ò gbọ́dọ̀ já ìbàlé kótó relé ọkọ before a girl must not lose her virginity before marriage
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#iroyin, #yoruba, Alufa ijo katoliiki dojuti Gomina Ortom, o ni opuro ni: Ojo itiju gbaa ni… https://t.co/xfbqcTSSJA
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Tí gbogbo ọmọ Nàìjá tí wọ́n wà lẹ́hìn odi bá padà wálé. Àwọn t'ọ́n ní láárí ni o. Irú àyípadà rere tí yó débá Ilú!!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọlèrè ayé. Ẹ jọ̀wọ́ ẹ dá àwọn ọmọ wa padà #AyajoOjoEwe #BringBackOurGirls http://t.co/BU2dQo7aYL
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#iroyin, #yoruba, Ooni di babaasale CALDEV, lo ba seleri atileyin fun idaabobo eto awon ewe… https://t.co/VD8iqsVcQR
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ah ó kù díẹ̀ kódà tí ẹ bá sọ òkúta ní òkukù tí ò bá jábọ́ sórí òrùlé kan nílù u wa díẹ̀ níó kù
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀wàrá òjò látalẹ́ àná, àwọn kan sì ní ẹ̀fúùtúẹ̀tẹ̀ ni ọ̀rọ̀ àyípadà ojú ọjọ́, wọ́n ní irọ́ ńlá ni. Òjó ti rọ̀ fún wákàtí mọ́kànlá💧 Látọjọ́ tí mo ti gbọ́njú, n kò lérò wípé ọjọ́ pọ̀ tóyìí lóṣù kẹwàá. Ńbo layé ń lọ ẹ̀yin ènìyàn! 🌧️🌧️🌧️🌧️🌧️🌧️🌧️🌧️🌧️🌧️
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
2. Àwọn ìyáàmi àjẹ́ ni à ń pè ní òṣàlà-ǹ-ṣolo, òṣòlò-ǹ-ṣala, àwọn ọlọ́dẹ ni à ń pè ní ògúngbè, àwọn wo ni à ń pè ní ọ̀pàpàpagidà-sọgidèèyàn? #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mo kí ti ìbàdàn olúyọ̀lé ẹ̀yin ọmọ láyípo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ní àárín Ilẹ̀-Ifẹ̀ ni igi ọ̀pẹ t'ó ya búkà 16 wà, igi ọ̀pẹ̀ yìí ni Ọ̀rúnmìlà bá wọ ọ̀run lọ. #Eerindinlogun #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àjànàkú ti ń dohun ìgbàgbé àgbọ̀nréré náà ńkọ́ àwọn jagunlabí inú igbó ti fẹ́rẹ̀ẹ́ pa ẹranko oníwo àrà níwájú àtàrí tán ẹgbẹlẹmùkù owó ni wọ́n ń ta ìwo àrà náà
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Èmi náà dúpé lówó Elédùà. A kìí bólókùnrùn eye lórí ìté. Mo júbà Òbángíjì. #ekaaro
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí ìgbà-á bá ń gbáni, ká máa rọ́jú, nítorí ìgbà sì ń padà bọ̀, tí ìgbà yóò tún gbani sílẹ̀ lọ́wọ́ ìyà. #EsinOro🐎 #Yoruba #COVID19
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Kosi otutu ni ilu eko ...gbogbo ibi kiki oru. """"""""@user: Ọ̀gìnìntìn dé o. http://t.co/JSa2Oi2p""""""""
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
awon omo ile igbimo asofin agba orile ede naijiria ti so oro won di ati fi oje bo oloosa lowo o ku baba eni ti o bo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìyáa wa @user sọ púpọ̀ lọ́rọ̀, ó rọ ọ̀dọ́ láti f'ọgbọ́n inúu wa ṣe ẹ̀rọ ayárabíàṣá fún èlò ẹ̀kọ́. #SMWBetterEdu http://t.co/FG4BMccRRH
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Eni ba mo ore afope fun olore""""""""@user: Èmi ni ajíṣọpẹ́, ajídúpẹ́, ajígbóríyìn f'Ọ́lọ́run Ọba. Nítorípé Ọlọ́run Ọba ...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user @user B'ónílé ò f'ura olè ni yóò kòó.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Yoòbá tún wípé Ọmọdé gbón Àgbà gbọ́n ni wọ́n fi dá'lẹ̀ Ifẹ̀. Dandan ni kí tọmọdé-tàgbà kópa nínú àtúnṣe yìí
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Níbo ni """"""""bìlísì"""""""" ti wá? Bá wo ni ọ̀rọ̀ yìí ṣe wọ inú èdè Yorùbá? #AyaloEde #Yoruba #learnYoruba #OroAyalo https://t.co/7vVWUejUrX
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Omo Oduduwa tokàn tokàn ...Yoruba ni mi 💯 #yoruba #backtoschool #Arewa #yorubadboi
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user nitori omo eta nii koko ta ki omo eranko too ta, tilu bata ba yo loke ijo ni teru tomo fii pade e. Iyi ni tiwa lojoojumo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọ Èkó wo bọ́nà ṣe rí, #Oworo sí #Anthony náà ni @user http://t.co/tA6Y4xPpxb
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
8. Ṣe ìṣirò ìsọdipúpọ̀ wọ̀nyí : 100 X 5 = 20 X 6 = 5 X 4 = #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: won wiiree!!!""""""""@user: Onímọ̀ oúnjẹ fún ìlera ní kí a máa jẹ èso mọ́ngòrò dáadáa pé ó ń lé jẹjẹrẹ, aàrùn ọkàn àti o…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹ mà ṣeun o. Kòsí láburú o. Ọ̀nà ló pọ̀ díẹ̀. Ẹ kú àìríni-béèrèẹni o. Ọlọ́run á tìyín lẹ́hìn o.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user ti eru ba kan oke to kan ile, o tun ni ibi kan a gbee ka . owe #Yoruba #TweetYoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
6. Kànrìnkàn ⏩ kàǹkàn Irun àgbọ̀n ⏩irùngbọ̀n ________ ⏩ ààtàn #Ibeere #Yoruba #learnyoruba #Language #isunki #iparoje
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ní ìparí ọdẹ ni à ń pè ní ògúngbè
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Èpè ò jà b'ẹ́nìkan ò rọ̀ ọ́. #EsinOro #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
omo ti ao ko ni ogbe ile ta ko taa
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Minisita oro epo ejo ko si obo mo ni ilu Idanre Ko si epo ni ilu ewan parowa pe entoji epo fun strategic reserve. Eye pe aja lobo fun mekunu
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kò fọwọ́sí fun sinimá. Eré yìí ni wàhálà púpọ̀.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Báwo lọ̀bọ́ ṣe ṣ'orí tí ìnàkí ò ṣe; tí iṣu fi ṣe orí gọngọ. Ẹ fún ìṣẹ̀ṣe lọ́ludé. #Iseseday #Iseselagba #Yoruba #Oduduwa @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ṣé ojú ogun ni? @user @user #EkitiDecides
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré ẹlẹwà,... Idapọ ohun gbogbo
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ìyẹn ni pé kìí ṣe ẹ̀wà ara àbí agbára lásán làá fí jọba àkọọ́ẹ̀ olódùmarè ni
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user: #Owe: Ẹni tó gbin òkúta sínú ebè tó pèé ni èbù iṣu, ìgbà tóníyán bá ńjẹ iyán òun náà yóò máa jẹ ìka. @user"""" #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Sinimá yìí burú débi wípé, kò sí àsopọ̀ láàrin ìbẹ̀rẹ̀ àti àwọn apá tó kù. Èyí kò bójúmu ṣùgbọ́n sinimá yìí lè dára jù báyìí lọ.
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user """"""""Ore ofe olorun ni koko"""""""" -#Yoruba 🇳🇬
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user #Atunse A à rí i ooo - ó yẹ kí a máa kọ ọ́ ní ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni, a kò gbọdọ̀ kọ ọ́ papọ̀, àfi bí a bá ṣe ìsúnkì. Aàrí kò tọ̀nà, 'a à rí i' ni ó yẹ. A à rí i náà ni a ò rí i. #Ami #Yoruba ❤️
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user In my Yorùbá mind, I'll translate this to """"""""Ẹ má f'ata pa mí""""""""
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹbọ kàǹkà wo ló fẹ́ ka igún mi láyà
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kí lẹ rò pé ó wá fa ìdíwọ́ wa àbí àwa kọ́ ni òmìrán afirika mọ́ ni
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìtumọ̀ Yéjídé jinlẹ̀ púpọ̀. Ọmọ tí a bá bí láìpẹ́ sí ọjọ́ tí Ìyá-ìyá tàbí ìyá-Bàbá ẹ̀ bá kú ní à ń pè bẹ́ẹ̀. Ǹjẹ́ ìwọ náà fẹ́ràn láti mọ ìtumọ̀ orúkọ rẹ, fi àtẹ̀jíṣẹ́ orúkọ rẹ ráńṣẹ́ sí wa ko sì tẹ̀lé wa lórí ìkànnì ayelujara yìí. #yoruba #yorubanimi https://t.co/iHPDXlCFu8
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Àṣẹ wàá bí eni là'rèké.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ope o mo pari abala akoko ise yii Eledumare ran mi lowo dele o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""Àwọn gómìnà ń ṣe ìgbéyàwó fọ́mọ wọn nígbà tí Boko Haram ń ko àwa lọmọ lọ"""""""" Olóòtú Sahara Reporters tí fọgba yángan htt…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user Ewúrẹ́. Láì kú ẹ̀kìrì, a ò gbọdọ̀ fi awọ rẹ̀ ṣe gbẹ̀du.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
8 » Wọn kì í gbé wọọ́n sin. #Eegun #Yoruba #Oyeku
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train