text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
@user @user Fùkù ni ẹ̀yà ara tí ó ń gba afẹ́fẹ́ tí a mí sínú. A lè tún pè é ní """"""""Ẹ̀dọ̀ Fóóró"""""""" | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré yìí fi bí ẹ̀sìn tí wọ̀ wá lára ni Nàìjíríà. Àwọn ènìyàn àti ìlú Èkó tí wón lò jọjú.. . N kò tilẹ̀ lè sọ bí mo ti wo gbogbo eré yìí tán. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
ìbọ́sáfẹ́fẹ́ fún ìgbà àkọ́kọ́ ní 31-10-1959. Ìdí tí wọ́n ṣe da sílẹ̀ ni láti jẹ́ ohun ẹ̀kọ́ fún àwọn ará agbègbè náà, àti láti tan ìmọ́lẹ̀ sí àṣà, láti gbọ́ ìròyìn òkè òkun, àti láti lè mú ohun ìṣèjọba wá sí ìmọ̀ àwọn ará agbègbè náà. Àwọn eré òyìnbó bíi | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé àjẹnù ìrèkè a máa fa àkéréke bí ohun aládìńdùn ṣe ń fa kòkòrò | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ṣágo ń bú ìgò, èèbó Jaap@user, BrendaBleek kọ Iré fún Ire, @user ọmọ Yoòbá kọ Oódua fún O'òduà. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eleyi ka mọ mọ! #TweetInYoruba https://t.co/sFi7ok7Clq | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ tètè fi ẹni ẹlẹ́ni sílẹ̀ o, ohun tí a ní kí òkóbó yín bọ̀, ẹ ò bọ̀ ọ́, ẹ lẹ́ ẹ ó bọ igba abẹ́rẹ́. Fúlàní ń fara ni wá! @user @user | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ise ti awon ara ilu ran mi ti bere ni perewu - Gomina @user ti o wole leekeji l’Osun ni o so be | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àkùkọ t'ó kọ lánàá, Ìkọ rere l'ó kọ. Àkùkọ t'ó kọ lónìí, ìkọ rere l'ó kọ. Á dára fún wa, ire lojú owó ń rí, ire la óò máa rí. #Iwure | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Rising Voices’ Activismo Lenguas gba Àmì-ẹ̀yẹ Èdè Abínibí Àgbáyé. https://t.co/8uQKHEVwLx @user @user @user… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ewu ń bẹ lóko longe fún ọ, jọ̀wọ́, ṣe ìwọde ìfẹ̀hónúhàn oniroworose, èyí a máa mú ìtìjú bá àwọn aninilára ni. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀gúntìmẹ́yìn Ògún supports me. https://t.co/7Uu7DC3a9k | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Igbesi aye gidi lórí ère buruku, paapaa lati ọdọ awọn onijagidijagan ni fiimu yii | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Àìná, orí ẹ wà ńbẹ̀! Mo fẹ́ràn ọ̀rọ̀ àpèjúwe ọmọ-adú tí o lò nínú orin #AfricanLady. ♥ #Melanin #Yoruba @user https://t.co/5NaIbpyZFH | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Erin arin takiti o ;) RT""""""""""""""""@user: @user Ọlọ́run Ọba."""""""""""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Arábìnrin wa àtàtà. Ẹ mà kú ìdìde o. Ládùn ládùn làá bá'lé olóyin o. Ẹṣeun. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Elo da Egbe tiyin sile, abi ewo ni soboloke, ariwo lenu fendo lori egbe elegbe, esa ti gbe apoti ibo, ede ti fi idi re omi. https://t.co/gAGA9xpvPw | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ kú àṣálẹ́ o! #yoruba http://t.co/fXIywYCt0h | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ó tọ́jọ́ mẹ́fà kan o mowa pa o ile ise yin koni jona o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọbẹ̀ òṣíkí ẹlẹ́ja àrọ̀-irà tí ó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ irú nínú, pẹ̀lú olú, ni ẹhùn t'ó hùn mí í jẹ. Ọ̀rẹ́ẹ̀ ẹ̀bà. Èyun-ùn lọbẹ̀. 😍 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àníjó fujì l'á rinrin Ẹ lè bẹ̀rẹ̀ mọlẹ̀ k'ẹ ma rá Ẹ lè wà upstanding k'ẹ ma jo 🎶 @user @user https://t.co/gND4pQO0WO | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ̀yin tí ẹ ṣe adọ́ta lẹ ó ṣe ogọ́run ọdún láyé | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wọ́n fi irin bò wá lẹ́nu kí a má baà jẹ ìrèké tí a gbìn. - """"""""""""""""Our mouths locked for us not to eat the http://t.co/SQqu16bxU2 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ìràwọ̀ ọ̀sán gangan tó ohun tí gbogbo àwọn àgbàlagbà ńpéjọ wò. / A star that shows up at noon merits the undivided at… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ojúmọ́ ire ni mo jí sí | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
PÀTÀKÌ ÌLẸ̀KẸ̀ ÌDÍ SÍ ÀWỌN YORÙBÁ (1): JÍJÍ ARA ỌKỌ SÍLẸ̀ Àwọn obìnrin Yorùbá ma ń wọ ìlẹ̀kẹ̀ ìdí, láti ara ìgbàgbọ́ wípé, ó ma n jí ara ọkọ wọn sílẹ̀ fún eré lọ́kọ-láya. Ìlẹ̀kẹ̀ yìí sì wà fún ọkọ wọn nìkan láti rí. Tí aṣọ sì ma bòó ní ìta. https://t.co/WK3LtCU5jz | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
baba mo dé mo wá gbare tèmi | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Awon eniyan kan wa ti won kii fi itan lukuru si oju ewe twitter won. Emi kii tele iru awon bee | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ÌTÀN ÀTẸNUDẸ́NU LÓRÍ BÍ WỌ́N ṢE TẸ̀DÓ ÌLÚ IGBỌ́N Ìtàn fi yé wa wípé, ọkàn nínú àwọn ọmọba Ifẹ̀, tí ó wá láti ìran Odùduwà, èyí tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́, Ẹsẹ ni ó yẹ ìlú Igbọ́n dó. Òhun ni Olú àgbàlá Ọgbọ́n Mọ́run ní Ifẹ̀, tí wọ́n sì ń pè é ní Olú-Igbọ́n. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ní #UK, àwọn agbófinró ọlọ́pàá ò kí n gbé ìbọn. Òfin ilẹ̀ náà kò fún ẹnikẹ́ni ni ààyè àti ní ìbọn rárá. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ ṣe é ! Thanks for the shout out! #YorubaNames https://t.co/ZTeQxC0j6c | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òfófó ilé yìí á yẹra (×2) K'á má gbọdo s'oro K'á má gbọdo j'ẹnu wúye Òfófó ilé yìí á yẹra"""""""" The talebearer in this home must make way. One dares not talk, Nor dares whisper. The talebearer in this home must make way #Yoruba songs are replete with expressions that signal1/2 https://t.co/DAfsLXcMH7 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ká mọ́ purọ́ ọ̀ràn an ká mí lára gógógó torí kò sí n ó ṣe | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Alagbada Ina, Alawotele Orun, Alaabo, Oluso, Olupamo, Oludande, Olugbala, Olutusile, Oludariji | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user haha. ọmọ yìí má pamí o | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
A lè ti gbàgbé, àmọ́ ẹ jẹ́ n rán an yí létí pé iṣẹ́ àgbẹ̀ niṣẹ́ ilẹ̀ wà, ẹ jẹ́ a ṣe é, fún ànfààní wa ni. #IseAgbeNiseIleeWa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
BITTERLEAF can also be called EWÉ IMADÙN in Yorùbá. Meaning, sweet leaf. Orúkọ òmíràn tí a tún lè pe EWÚRO ní Yorùbá ni """"""""""""""""EWÉ IMADÙN"""""""""""""""" (ewé tó ní adùn). https://t.co/PTvLbJtVt2 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bí ẹ bá ṣe òfin tótó, ẹ ó rí ohun èlò ògbufọ̀ sí èdè mìíràn, bí tinú àwòrán wọ̀nyí. Èyí ni #TweetYoruba dúró fún. Àlàyé ni bàbá ọ̀rọ̀. https://t.co/dCz87OP8N2 | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Ah, a dúpé l'ówó Elédùwà sà. E ñlé sà, e kú ojó méta... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ kú ojú lọ́nà ooo #TwitYoruba fẹ́ẹ̀ẹ́ dé o. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""""""""""... Ní ọjọ́ kan báyìí, ọjọ́ burúkú èṣù gbomi mu, tí ìjà ń lọ níwájú, ni ìṣẹ̀lẹ̀ ńlá kan ṣẹlẹ̀. Ṣe ńṣe ni gbogbo ọkọ ogun,… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ jẹ́ k'á para wa láyò. #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo fẹ́ o ṣe nǹkankan, wá tàgíìrì, lu ú kí o rí bí omi inúu rẹ̀ ṣe rí. #Tagiiri #Ewe #Eso #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn apá kan nínú eré yìí dá bíi àgbélẹ̀rọ lórí kí àwọn òșèré méjì lè rí ǹkan jà sí. Àwọn òșèré kọ̀ọ̀kan gbìyànjú bẹ́ẹ̀ àwọn kọ̀ọ̀kan kàn ń mú inú bíìyàn ni. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
ewé olówójẹja etípònlà àwọn oníṣègùn á máa lò ó fi ṣe àyẹ̀wò oyún lára obìrin | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Tí lágídò bá ńfò láti orí igi kan sí èkejì, àwọn tó ńwòó ló rò pé eré ló ńṣe; òun fúnra ra rẹ̀ mọ̀ pé akọ iṣẹ́ lòun ńṣe @user #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìdójú tini ni | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ẹnikan ko fi asọ silẹ ni edidi lakoko ti o n ṣe adehun lori rẹ. An old #Yoruba proverb which means: “One does not leave cloth in a bundle while bargaining over it.” • (It is wise to know what one is negotiating to… https://t.co/lBs8RYYrVY | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Tí èyàn bá ní sùúrù, ohun tí kò tó, ṣì ńbọ̀ wá ṣẹ́kù. / #Yoruba If one is patient, what is insufficient will soon be excessive. [Patience is crucial. . . Be patient] | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wọ́n á ní Ògbómọ̀ṣọ́ Ajílété. Ẹ jọ̀wọ́ kí ni ìtumọ̀ ajílété o, ẹ̀yin ọmọ Ògbómọ̀ṣọ́? @user | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ṣé pé #JPMorgan ni owóo epo rọ̀bìi wa wà? | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Èèyàn mi, mo wà jàre. A kú ìgbélé náà, Èdùmàrè á kó wa yọ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eni ti yoo daso fun eni torun re laa ko wo, to difa fun pastor to ra oko baaluu aladani, to wa n wasu pe kawa to isura wa jo si orun :-( | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àṣesílẹ̀ làbọ̀wábá ẹ jẹ́ á ṣiṣẹ́ ajé lásìkò àárọ̀ kí ọjọ́ alẹ́ tó wọlé dé kí a ba fi ẹ̀yìn tì jọrọ̀ lálẹ́ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Músò! Músò! Músò! Ọmọ ikọ̀ #RealMadrid, ẹ kú oríre o. Ó yá músò, músò, músò ... #idanoripapa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Iba Gani Abiodun Ige Adams Aare Ona Kakanfo of Yoruba land @user the Installation of Princess Toyin Kolade Iyalaje Oodua Held Today at Ile Ife Osun State. #oodua #odua #yoruba https://t.co/qYgeRtfO82 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
yàtọ̀ sí tàkúté àti oògùn pekupeku ó tún ku ìkan tí àwọn bàbáńlá wa ń lò fi lé èkúté ilé | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
.@user Bí yànmùyánmú bá kẹnu rẹ̀ ṣoṣoro bọ ènìyàn lára láti mu ẹ̀jẹ̀ t'ó wáyée rẹ̀ wá mu, ó ṣeéṣe k'ó gbé àìsàn ibà wọ ara onítọ̀hún. #AyajoOjoIba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Jegudujerani nii ooo #TweetinYoruba https://t.co/u2eqHPcdwx | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
oògùn tí a fi ń de oyún mọ́lẹ̀ kí ó má ba bàjẹ́ pọ̀ ganan | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: #wednesdaymorning #WednesdayVibes #Yoruba Àfowófà ni ó pa èkúté ilé Nígbà tó jeun tó yó tán O ránsé pe ológbò O ník… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Lóòótọ́ ni pé orí adé kì í f'orí balẹ̀ fún orí adé, lẹ́yìn èyí """"""""Abọrẹ̀"""""""" kò gbọdọ̀ dọ̀bálẹ̀ tàbí f'orí balẹ̀ fún ọba. #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
iṣẹ́ ti tán lónìí ó ku ká rọra gbafẹ́ díẹ̀ atẹ́gùn àláfíà nfẹ́ orin aládùn nlù lórí àwo ìpanu náà ò sọ̀wán ìgbádùn ni rẹpẹtẹ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
láfikun sí i àsìkò òjò ni ohun oko máa ń ta jùlọ nínú ọdún bọ̀kùàbọ̀kùà ni ohun ọ̀gbìn yóò ta | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àyárá-Iná! Ká-bi-kò-sí! A kú Ọjọ́ Ọ̀sẹ̀ Ṣàngó o gbogbo ọmọ Yorùbá. https://t.co/oP7Gvv4Mmg | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Orúko àmútòrunwá Yorùbá. Yoruba predestined names. (Kó omo re episode 29) . . Full video on YouTube[ Yoruba Pikin ] Teacher: @user Students: @user ( Yacoob, Adam and Kamil ) #asa #culture #yoruba #yoruba_pikin #lekan_kingkong https://t.co/QMJV8JFEQR | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọ̀rọ̀ ọjọ́ òní dálémoṣú obìnrin tí ó ti ní ọkọ ṣùgbọ́n tí ó kó ẹrù rẹ̀ kúrò nílé ọkọ padà sí ilé bàbá rẹ̀ tí kò padà sí ilé ọkọ rẹ̀ tàbí kí ó fẹ́ ọkùnrin òmíràn | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: 12. Orúkọ mìíràn fún : Ejòlá ni erè Erin ni àjànàkú ____ ni èkùté-ilé #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọ̀kan lára eré ìdárayá Yoòbá ni ayò ọlọ́pọ́n títa. Kí ní fà á tí a fi pòwe pé """"""""bí alẹ́ bá lẹ́ à á fi ọmọ ayò fún ayò"""""""". #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Alaafia la wa o otutu die kan n mu ni nitori ojo ale ana""""""""@user: Ẹ kú ojúmọ́ o ẹ̀yin ẹ̀dá rere. Ṣ'álàáfíà ni? Ṣẹ́ dáadáa"""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ese ko oo kii si se ibinu olorun ise owo awon arije nidi modaru ni lati orilede awon chinko | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
gbogbo ẹni tó ń gbaruku tí mímo rò yín láti ko ara yín ní íjanu pẹ̀lú ọpọlọpọ irele kódà sì gbogbo àwọn tí kò faramo èrò yínèébú èké àti idunkoko moni yóò wáyé ẹmáa ṣe bìkítà bí kò ṣe pé kí ẹ ní àfojúsùn lọ́nà àti wa ọ̀nà ìlọsíwájú fún orileede naijiria | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eni tí a bad fi ori re fo agbon ko ni le he nibe,.. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Eniyan laso mi (People Are My Cloth) by Niyi Osundare. #Poem #AfricanPoetry https://t.co/4vSKlpiGnk | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
#TweetinYoruba E' ba mi gbe jesu yii gaa, Ehn a Ehn🎶 | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Kùtù-kùtù kìí jóni lẹ́sẹ̀ bí ọ̀sán. Kí olúwarẹ̀ ó yáa n'de lórí ìbùsùn kíá-kíá. #ekaaro o. A à jí bí? | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wọn yó kọrin dé ilée rẹ̀. Bí wọ́n bá dé ilée ọ̀bàyéjẹ́, láti ìta ni wọn yóò ti máa sọ òkò tàbí da iyẹ̀pẹ̀ lu ilée rẹ̀. #Kirikiri #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ayé nlọ a ntọ̀ọ́!! | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Iwájú lọlọ́kọ̀ yí nwà mí lọ...♫ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Omo Ifewara ni emi na o, Ikogun ni ile wa sugbon Ibadan ni won bimi si #TweetinYoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Olódùmarè àwa gbé Ọ ga. A dúpẹ́ fún ìṣọ́ àti àbò Rẹ. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bábá bo bàbà mọ́lẹ̀. #Owe #Yoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
gbogbo ẹ̀sìn ti dìde. Gbogbo ohun tí ó ń wàásù yẹn, jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìtàn ẹ̀sìn tí ó tara ìtàn ẹ̀sìn tí ó ti Ifẹ̀ jáde. Wòlíì Samuel Johnson, Ajíhìnrere Yorùbá ti ìjọ Anglican, lọ sí Ìbàdàn ní ọdún 1882, ní ibi tí wọ́n ti sọ fún wípé, Ifẹ̀ ni ibi tí gbogbo | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Omodo agba Pari owe yii.. #yoruba #culture #osun #isese #oduduwa https://t.co/LI98305ZaU | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
in this era books of such importance are made open for the common good àǹfààní tí ó pọ̀ jaburata ní ń bẹ níbẹ̀ bí ohun àmúlò bí èyí bá wà ní ìṣísílẹ̀ gbangba wálíà fún ẹnikẹ́ni láti lò | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré náà burẹ́wà | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
...ó rántí pé ẹran lòhún wá pa lọ́gànjọ́, ó yára tájí. Iwájú tí ó wò, kí lẹ mọ̀ tí ó rí? #itan #oremeji #yorubaculture #yobamoodua | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
13. #Parioweyii : Ibi tí a bá ti sọ wípé ó dàárọ̀... #Ibeere #Yoruba #owe | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
who remembers this song lọjọ àjíǹde lọjọ́ àjíǹde àwọn obìnrin lọ sọdọ̀ jésù àwọn ọkùnrin lọ sa pamọ́ sábẹ́ igi a kú ọdún àjíǹde o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìtẹ̀síwájú l'ọ̀pá ìṣẹ́gun, máa ṣẹ́gun, ó di dandanǹdan. Nítorí bí orí bá pẹ́ nílẹ̀, á d'ire. Ìgbégaà mi ò pẹ́ mọ́. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kòsí agbára kankan n'bì kankan tí a le fi wé ti Ọlọ́run Ọba. #ekaaro | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ìpele ṣíṣí jẹ́ olùránnilétí tí àwọn ìpele ìbẹ̀rẹ̀ tí àwọn eléré orí ìtàgé, kìí ṣe ni ọ̀nà tí ó dára. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
sebi agbejoro ni wan pe ologbeni yi se ti oba de ile ejo aruwo processing ni oma ma pa fun adajo oro yin su mi o | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ti e ba gbe ina kari,e ba ekun mi ni buba. #TweetinYoruba | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Òòrùn tó kù lókè tó aṣọ ọ́ gbẹ. / The remaining sunlight is still good enough to dry the clothes. [Keep hope alive: d… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
mo kí gbogbo ọmọ naija káàkiiri àgbáyé ẹkú àyájọ́ òmìnira o ọlọ́run ọba á fúnwa ni òmìnira o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
4. Fáwẹ̀lì ahánupè, iwájú, pẹrẹsẹ àìránmúpè ni """"""""i"""""""", fáwẹ̀lì wo ni """"""""in""""""""? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
a fún ìdí àti ṣèpamọ́ ìtúàṣírí ìfitónilétí tó wọlé lóhùnawo ní ìmúṣinṣinagbáraàṣẹ àti òmìnira iléẹjọ ́tàbí ìṣàkósoìdarí ìfohùnránṣẹ́ ìgbésáfẹ́fẹ ́alátagbàìmóhùnmáwòrántàbí ìṣàfihànníta ìtàwòránsáraaṣọtàbí b fúnìpọndandanàwọn | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Akowe ko wura, lo wa di tiratira. """"""""@user: Ẹ mà kú ọjọ́ mẹ́ta o ẹ̀yin ẹ̀dá Ọlọ́run wọ̀nyí. Bóo ni o?"""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ̀wẹ̀ a gbọ́ wípé lẹ́yìn ìgbà tí ìyá ńlá di òrìṣà, ọkọ rẹ Bàbá Abọrẹ̀ gba ijó o rẹ̀ jó. #Gelede #Yoruba #Ifa | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.