text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
@user @user @user. Daadaa la wa o oke ihin ni ko je ki a ri tohun o jare
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user — Ire ni oju owo nri, ire ni oju ojo nri..... Ire loni ori wa afi ire..... Eledua koni je ki a se ise f ...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ko kin se gbogbo WIFI lo le lo, sora fun awon ti o fe se ijamba si ero ibanisoro e Dabobo WhatsApp e, lona Meji pelu numba apamo (password) Ko awon osise ile-ise e nipa Idabo ero ayelujara. #Cybersecuritytuesday #Cybersecurity #yoruba https://t.co/pSn5P2LrZT
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
wàyí o orun ló kàn ṣebí ẹ̀yin náà lẹ ní ará fẹ́ sinmi à á jí pé o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ìyá Sofie Olúwọlé ń ṣàlàyé ìyàtọ̀ Èṣù àti Sátánì. #Esuisnotsatan #Yoruba https://t.co/gjcDtThiAi
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Bí èmi ṣe máa n sọ̀rọ̀ lórí Twítà rèe
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user ìyá dáadáa, ẹ kú àyájọ́ ọjọ́ ìbí o, bí ọdún bá kan ọdún, pèrègún á mú àwọ̀ tuntun wáyé. Ẹ f'àkàrà òyìnbó ṣ'ọwọ́ sí mi o!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user e se gan! Ojulowo omo Oodua ni yin.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ise Òṣeré tí ó pè dé gé tí ó sì ní ìmọ̀lára gidigidi. Ìtàn na lágbára.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ipín márùn-ún ni mo ti wò.... Mo fẹ́ràn rẹ̀
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
kíni ohùn n tòun ṣẹlẹ̀ ní bí? . . Eré yìí burú gan ni, lójú kan ó ma rò wípé ṣé òún wo kọ́mẹ́dì ni tàbí Eré oníṣe
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Ìkọ́, ìgèrè àti àwọ̀n ni àwọn ohun èlò apẹja. #Yoruba #IseIbile https://t.co/yRmqWvDf6M
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
oríṣirísi ni adé nílẹ̀ yorùbá kíni à ń pe adé tó wà lórí ọ̀jájá kejì yìí
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#iroyin, #yoruba, Owo olopa ti te Gbemileke to ji isu l'Ajebandele: Tolulope Emmanuel… https://t.co/MGeVRGitUd
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ebemi nbe niwaju re oba orun gbaa wole ki enu leeya awon alayonu so ki oju ki ole ti awon ti won ro pe kolee sese amin
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wọ́n ń lo ọpọlọ wa, àmọ́ a ò mọ̀. #Subliminally ni wọ́n ń pè é léèdè Gẹ̀ẹ́sì. A ò fura #BringBackOurGirls @user @user
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: O ò rí òògùn aláròká se/ there’s no charm to stop a back biter. #oroiyanji #yoruba #subtitled https://t.co/A6DYWT42j2
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Agodo níbi tí Adímú Òrìṣà yóò kọ́kọ́ lọ láago mẹ́fà sí méje òwúrọ̀ lọ́jọ́ kejì sí ọjọ́ Eré Ẹ̀yọ̀. #EyoOrisa #Lagosat50 #EyoFestival #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ÒWE / PROVERB Bí a bá ń kìlọ̀ fólè, kí a kìlọ̀ fún oníṣu ẹ̀bá ọ̀nà. TRANSLATION: As we warn the thief, we should also warn the farmer who plants yam beside the foot path. ÌTÚPALẸ̀: bí ó ti jẹ́ wípé, olè jíjà kìí ṣe ohun ire, ẹni tí ó gbin iṣu sí ẹ̀bá ọ̀nà náà...
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user Lọ́jọ́ Ajé, olobó ta mí, mo gbọ́, àwa ló kàn láti gba ẹ̀tọ́ọ wa. Mo ra èpò s'ọ́kọ̀, mo f'orí lé Òkè Mọsàn l'Ábẹ́òkúta. #PapakoOfuurufu
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Awọn ọna Meji - Apá 3 “Ẹ gba ẹnu-ọna to muna, nitori titobi ni ilẹkun, ati titobi, ọna ti o lọ si ibi-iparun, ọpọlọpọ ni o wa ni iwọle. wa i. ” Mátíù 7: 13-14 #Ọlọrun #Jesu #EmiMimo #Bibeli #niife #Igbala #amojukuro #yoruba #Ioruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Bí #Charleyboy sí #Anthony ṣe rí nírọ̀lẹ́ yìí rè é. Àwọn ti ọ̀nà #Ikorodu ló fà á o @user http://t.co/2Yu5IcBgrh
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Fun Mi Ni Nomba Ero Ibanisoro Re TonLo Fun Wasaappuu #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ta ni ẹni tí ó kọ́kọ́ ru àgọ̀ egúngún
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ataare, iyọ̀, àádùn, oyin, omi, ìreké, ọtí, orógbó, obì...abbl #isomoloruko #yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìtàn idile àti ogun. Mo fi taratara fi ọwọ́ sí eré náà.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
agbo wipe ni ojo ajinde awon obirin lo sodo jesun awon okunrin lo sapamo
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bẹ́ẹ̀ni a kúkú ní tìróò là ńpè é bo bá jẹ́ ojú ṣe ipin tàbí ojú ńgún ni àbí kẹ̀ ojúu yín ńṣomi ẹya tètè wá tìróò kí ẹ máa lòó
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ere idaraya: Akoni mogba fun RealMadrid Ancelotti ti so wipe kodara ki agbe gbogbo ebi fun Balotelli nitori igbakugba LFC @user…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹ̀ ẹ́ jèrè!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ní ìsàlẹ̀ Èkó, a gbọ́ wípé Amùkòkò ní í kéde ìbẹ̀rẹ̀ ọdún Gẹ̀lẹ̀dẹ́, yóò sì kásẹ̀ Ẹ̀ẹ̀fẹ̀ nílẹ̀. #Gelede #Yoruba #IWD #IseseLagba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ibi tí ọká bá ká sí ni oúnjẹ rẹ̀ tí wá ń bá a. Oúnjẹ tí ajá yóò jẹ, Èṣù yóò pèsè. Olódùmarè! Gbé oúnjẹ tí n ó jẹ́ kò mí, pèsè fún mi, Ọba Olùpèsè. #iwure
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
saturn ló ni saturday oòrùn ni à ń bọ lọ́jọ́ sunday àwọn orúkọ ọjọ́ wọ̀nyí ti yí padà àbí ó sì wà bẹ́ẹ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
children are the leaders of tomorrow awon omo rere biiyan omo rere leyin wa ola toju omo re ki won o le fun e ni isinmi olodumare ko ni fun wa lomo gba je n sinmiooo aseooo ireoooo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Ayọ̀,àlááfíà àti ìlera to péye ni Ọlọ́run afi fún wao__ @user @user @user @user @user…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
gbàgede = field ground venue èrò pọ̀ ní gbàgede ètò people are many on the event ground
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
GiSTAS mi ọ̀wọ́n, Kẹn tíì kẹ? Ṣe dede ẹ jọ̀? #happymemorialday . . #lifeofagista #ondo #yoruba #makingyoulaughseriously #naijamoms #podcastmovement #tundeednut #nigerianamerican #africandiaspora #ekimogun… https://t.co/VMCqk2bDob
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àdó jẹ́ ohun tí àwọn Yorùbá ma ń tọ́jú òògùn (pàápàá jù lọ, bí ẹbu) sí. Wọ́n ma gé orí rẹ̀, kí wọ́n lè rí ibi rọ ẹbu náà sìí. Wọ́n wà ní oríṣi ìwọ̀n. https://t.co/3VPMyC0K05
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
kẹ́ ẹ fìfẹ́ bá wa lò ìfẹ́ wa ni kí ó wà lọ́kàn an yín bẹ́ ẹ bá ń ṣe òfin ìlú
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Olódùmarè mo fọkàntẹ̀ Ọ́, n mọ̀ wípé ṣíṣe ni tìrẹ, àìṣe náà tìrẹ ni. Ṣe é fún mi ì! N ò ṣıyèméjì, mo mọ̀ wípé o Ó ṣe é bí mo ti fẹ́. #Iwure
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òyìnbó kúu làákáàyè. Ẹ wo bí wọ́n ṣe fi amọ̀ kọ́lé alájà mẹ́jọ. Ó sì rẹwà gbáà! http://t.co/xCH6VLjs
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Onímọ̀ ìlera ní kí ẹ má jáfira, bí ẹ bá ṣàkíyèsí kókó, egbò ní àyíkáa ọ̀yàn tàbí ohun kóhun lára. #ISupportBreastCancerAwareness #Nigeria
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ire gbogbo di oríi wa. #iwure
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ara kì í ṣ'òkúta, bí àìlera bá sọ ará oko wò, ewé ni yóò já, egbò ni yó wà, ara rẹ̀ yóò sì padà bọ̀ sípò. Ọ̀fẹ́ nìwòsàn. #owoekoekolongbe
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
15. Kíni nọ́mbà òǹkà òjìlénírinwó lé mẹ́rin? #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
lára àwọn ohun tí a lè ṣe láti dènà ìtànkálẹ̀ kòkòrò cc
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Àìṣedédé ará ayé, ló ńmú’ni rántí ará ọ̀run. / The untoward behaviour of those alive is what makes us pine for those w…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eléyìí jẹ́ aláìdùn
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: A ni agbara lati yi eyi pada, ni bayi. Bawo? - lilo #Yoruba ati awọn ede Afirika miiran nibi lori @user siwaju sii.…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Apá lará, ìgúnpá ni'yèkan. Kí ni iyèkan? #ibeere #owe #Yorùbá
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ekuu Ayajo ololufe o. Happy Valentines Day. #kaftantv #kaftantvyoruba #kaftan #yoruba #yorubaculture #yorubanimi #yorubalanguage #instagram #africa #african #nigeria #lagos #ekiti #ondo #ogun #oyo #ibadan https://t.co/mjrsByQbJI https://t.co/qiLUtGUti8
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ka àwọn ìwé tí adú bíi W.E.B DuBois, Carter G. Woodson, John Henrik Clarke, Anta Diop, Yosef A.A.Ben Jochannan kọ kí àwọ̀n ojú ù rẹ ṣí.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orí tí yóò la ni kì í dẹ́rù pa ni
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kòókòó jàńjàń wa ò ní já sí asán, bẹ́ẹ̀ ni iṣẹ́ wa ò ní di ìṣẹ́, ọwọ́ wa á tó ire gbogbo tí a fẹ́, orí wa á kàn 'kè #Iwure #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#TweetinYoruba oruko mi ni Oluwatoyin Afolayan aya Oginni, abimi ni ilu ondo, omo ilu Efon Alaaye ni baba tobi mi lomo. Awa ni omo oloke...
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user Tani o mo ka fi eran si enu, ki Awa ti?
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹ ṣeun. A ti ń rí orúkọ ìwánilọ́kànwò yìí. Orúkọ tó ń jẹyọ kàkàkí àwọn àròkọ yín, tí ń mú ni, rín ẹ̀rín àrín tàkìtì. Tani ó ń jẹ Ajílàáláọ̀ṣọ̀ gan gan? Àti wípé, báwo ni orúkọ náà ṣe wáyé? Ǹjẹ́, ẹ lè sọ ìtàn ráńpẹ́ fún wa lórí rẹ̀?
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ǹjẹ́ ìwọ́ mọ̀ wípé aya Ọlọ́yọ̀ọ́ ti @user; Olúbùnmi Adésọjí Akínṣẹ́gun lẹni tí ó kọ́kọ́ rán aṣọ dànṣíkí ní America? #Yoruba https://t.co/qp90dh3eqk
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ò mọ̀ pé ìpínlẹ̀ ní àsíá ni láti ó dáa kí ẹ jẹ́ kó mọ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
A ti wọ ọdún tuntun, àwọn ọmọ yìí ò tí ì padà bọ̀dé o :( #BringBackOurGirls #Nigeria
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Láì sí ijiyan rárá eré orí ìtàgé yìí ní ó tíì dáa jù nínú àwọn eré ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Bí àkọlé eré yí ti dojú tíni tó, díè ni 'Makate Must Sell' fi yàtò sí 'Knock Out' tí Pápá Ajasco
negative
yoruba
NollySenti
movie_review
train
nkan ti fela ri to fi ko suffering and smilling niyen
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òkè Ìpá (Glover) ni a ti ń ṣ'Eré Ẹ̀yọ̀ látijọ, kí a tó gbé e lọ sí Ìdúmọ̀tà. #EyoOrisa #EyoFestival #Lagosat50 #Egungun #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àwọn kan mọ ìdáhùn sí mi wọn ò ní í sọ ọ́ àfi gẹ̀ẹ́sí ṣé ó dára bẹ́ẹ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ jẹ́ kí a ti ipa báyìí wò ó. Lákọ̀ọ́kọ́, àjùmọ̀ṣe, àjùmọ̀jẹ, àjùmọ̀lò, àjùmọ̀gbèèrò, àjùmọ̀ni l'àṣà wa dá lé. #OminiraNigeria #NigeriaAt56
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ooru naa ko ti kase nle ni naija bi otile jepe ojo ti bere rt òtútù yìí ò ní káwọ́ ńlẹ̀ ni ṣèbí a ti w
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Jíjí mo jí lónìí, mo jí s'ówó... Ire Ajé á kan gbogbo wa láṣẹ Elédùmarè. #IwureOwuro https://t.co/sPRUEVvKIn
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ará #New #Orleans gbogbo, Ẹkú ìgbáradì ti ìjì #isaac tó nbọ̀ o. Kí Ọlọ́run wà pẹ̀lú yín o.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Abala kejìlá. E̟nì kò̟ò̟kan ló ní è̟tó̟ pé kí a má s̟àdédé s̟e àyo̟júràn sí ò̟rò̟ ìgbésí ayé rè̟, tàbí sí ò̟rò̟e̟bí rè̟ tàbí sí ò̟rò̟ ìdílé rè̟ tàbí ìwé tí a ko̟ sí i; a kò sì gbo̟dò̟ ba iyì àti orúko̟ rè̟ jé̟. 1/2
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Amúnibúni ẹran Ìbíyẹmí; Ìbíyẹmí fọ́jú, ẹran rẹ̀ náà dití. Yorùbá ń gbáyé lọ, àwọn àpọ̀dà ò já. Ẹ ṣá máa wò mí. 😀
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ní 1844, ọkọ̀ 3,610 l'ó kó òwú wọ Liverpool , 6,995 wọ London, ọkọ̀ 2,473 kó òwú tí adú gbìn wọ Hull. #OIANUK
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
8. Gbóná bí aje Ga bí àgéré Tutù ju_____ Pọ́n bí òdòdó #Ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
gẹ́gẹ́ bí ọ̀jọ̀gbọ́ nnì wọlé ti sọ ó ní ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ mọ̀wé bíi tò n kólọ mọ tinú tìta èdèe abínibí rẹ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Wọ́n níṣẹ́ laago ń ṣe kú, síbẹ̀, ẹni tí kò bá nà ní ìpèbí, kò gbọdọ̀ jọba. Àṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní í ni 'ni lára.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
olódo mò ń gbádùnun rẹ bí ṣe ń gbádùnun jẹ́ ó wà bẹ́ẹ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Unmmm Oluwa ku suru........ https://t.co/BaQ4MaDrec
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Abo ni, akọ ni. Òṣakọ òṣabo ní í ṣe. #OroSunnukun
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user máa jábọ́ ìròyìn erée awọ róbótó aláfẹsẹ̀gbá lọ bí o ti ṣe ṣe nínú oṣù Agẹmọ, èmi gẹ́gẹ́ bí ẹnìkan fẹ́ máa rí irúu rẹ̀ lóòrèkóòrè. Ó dìgbà kan náà!
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Èkùrọ́ lalábàákú ẹ̀wà. Kí ni dúdú (òmíràn kì í dúdú) bí ojú tí ó wà lára ẹ̀wà ni à ń pè ní """"""""èkùrọ́"""""""". Ìperí yìí yàtọ̀ s'ékùrọ́ ẹyìn igi ọ̀pẹ̀. Bótilèwù kí á ṣe ẹ̀wà, yálà a gbìn ín ni, tàbí sè é lóúnjẹ, èkùrọ́ a máa bá a kú ni. #InYoruba #LearnYoruba #Yoruba #owe https://t.co/NDQoOj9iGI
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user @user #Alakowe2015 Alakowe ati Ore re: Eku orire o! K'oderun o... E fun bante yin daadaa o!!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Obe ki gbenu agba mi """""""" . . . #Owe #agbelero #yorubadun #yoruba #commissioner @user Ifm1005 Ibadan https://t.co/jy1cyVrfvZ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ara àwọn ohun tó mú kí òwò ẹrú gbòòrò ní ilẹ̀ yorùbá ni òwò ẹrú aláàdáani ní àwọn ìlú bíi ọ̀yọ́ ìjẹ̀bú àwórì ẹ̀gbádò abbl ìgbàgbọ́ ni wípé òwò àdáni ẹrú ló ṣe okùnfà kí ìjínigbé fi lọ sókè tí wọ́n sì ń ta àwọn ẹni tí wọ́n jí gbé sí oko ẹrú ní
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Káàbò! Sé dáa dáa l'o dé?""""""""@user: Ònìí lọjọ́ t'ó kẹ́hìn Ẹrẹ́nà, oṣù kẹ́ta ti fìdí jálẹ̀, ẹ bá mi kí oṣù kẹrin káàbọ̀! …
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Kini anfani orogbo? A be koni a we, a je o tun koro, a tun fe fi igi e da ina sango ni omo iya owun ni.... @user
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìjẹkújẹ ìwa wọ̀nbílíkí wọ̀bìà ti ba jẹ́ olórin oléré ìtàgé wa gbogbo ní ń wọ ìṣèlú láti jẹun sápò tirẹ̀ náà
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ÀWỌN Ọ̀RỌ̀/ORÚKỌ AGBOLÉ / COMPOUND NAMES (1): OÚNJẸ: ẹ̀bà, iṣu, gààrí, àgbàdo, ẹ̀wà, àsáró, kókò abbl Wọ́n ní orúkọ tí à ń pè wọ̀ọ́n ṣùgbọ́n, orúkọ tí ó pa wọ́n pọ̀ ni oúnjẹ They have their different names but, FOOD is the compound name
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
And on #Jumaat too, Aye o! #🙌🏼 #Friyayvibes . Gistas mi ọwọn, Barka de Sallah A bit different...but ẹrú dupẹ #gratefulheart #newnormal . . #lifeofagista #naijamuslimah #ondo #asalamualaikum #HGwR #yoruba… https://t.co/BVeUYqixED
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user àwọn ọ̀nà tuntun àti iṣẹ́ àtúnṣe tí mo ń rí ò jọ èyí t'ó lè t'ọ́jọ́ pípẹ́. Mo rí ti #Surulere lánàá, #Obalende lónìí.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Good morning everyone! Ẹ káàárọ o! Bawo ni ?
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
♫ Ké ṣe ń ṣe ọ́? Ṣemu-ṣẹ̀ṣẹ̀ṣe-ọ̀wẹ̀lẹ̀wẹ́lẹ́! Ké ṣe ń ṣe mí? Ṣemu-ṣẹ̀ṣẹ̀ṣe-ọ̀wẹ̀lẹ̀wẹ́lẹ́! ♫ #ElemureOgunyemi #Ekiti
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
️️ ikira fun egbe agbabolu ti won ma fi igba gbaga pelu egbe agbabolu ni ere papa ni ilu london
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nítorí wípé mo fi ọṣẹ ewé oríjì wẹ̀ lọmọ ènìyàn fi gbọ́dọ̀ foríjì ‘mí. #Ayajo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìdíi bàbá ni ọmọ bá okó #Owe #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹyin ọmọ àti ọrẹ Yorùbá àtàtà, ọmọ wa rèé @user , ẹ̀bùn fún gbogbo orílẹ̀ èdè Naijiria. Igbakeji ààrẹ @user , èyí tó ṣeé gbára lé, ọmọlúwàbí Yorùbá. Àwa ó ní ìkùnsínú kankan sí Peter Obi ooo sugbon in Yemi ni ìgbàgbọ́ wá wà. https://t.co/wrpmO39u5o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré àgbéléwò to dára púpò nii , àti pé gbogbo ènìyàn níi láti mò ní pa àwọn oun ti àwọn ìjọba ń fi àyè gbà ká ka kiri àgbáyé
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
ọba akínni a kì í ọba tí a ò gbọdọ̀ má kì í ọba òní àná ọba títí láí ọba ọlọ́wọ́ gbọgbọrọ o ṣeun jíjí ire
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọmọ inú odi, kì í kú sẹ́yìn odi. A ò ní kú láì t'ọ́jọ́. Ẹ kú ìsinmi ọjọ́ Àìkú o!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Fún àpẹẹrẹ: olojò. Victim ni olojò. #Yoruba @user @user @user @user @user @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ohun tí o jẹ́ pàtó láti jẹ ọmọ Nàìjíríà, Genevieve Nnaji kú iṣẹ́. Fíìmù tí ènìyàn gbogbo gbúdọ̀ wò, Naijiria saara rẹ,má tẹ̀síwájú.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train