text stringlengths 3 3.37k | label stringclasses 3
values | language stringclasses 3
values | source stringclasses 3
values | domain stringclasses 3
values | split stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
RT @user: Eje ka f'inu didun yin Oluwa Oloore,Anu Re yio wa titi l'ododo dajudaju.... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
7. Bí ènìyàn-án bá ṣu tán yóò fi omi nùdìí (fọ̀dìí). Yàtọ̀ sí fọnu, kí ni gbólóhùn mìíràn fún ẹni tí ó fi orín fọyín? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user Òtítọ́ ni. Àmọ́ ẹ ò bá gbìyànjú láti sọ Yorùbá ;) | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹrú ń bẹ, ìwọ̀fà sì wà, àmọ́ bí ìwọ̀fà bá san ọ̀fà rẹ̀ tán ó di òminira. Bẹ́ẹ̀ l'ó rí tẹ́lẹ̀. #nigbatiwonde | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Dágigé, gágigé, àáké kan ò le è dágigé. Dágilà dágilà, ẹ̀ẹ̀là kan ò le è dágilà. Bí ò s'Erelú àti Apènà, Òṣùgbó ò le è d'áwo ṣe. #EsinOro #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ajiire ope ni fun Olorun ojo ayo ni ojo naa yoo je, Ajinde ara yoo si maa je fun gbogbo wa | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo tilẹ̀ ń wa ilẹ̀ láàkọ́kọ́ Ere náà ni àkókò ṣùgbọ́n Oni ìṣòro ìfàyèsí ,o nilo í ṣàtúnṣe , àti pé otun gun | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
3. Kí nìdí tí a fi máa ń fi aró pa òrò-mọdìẹ lára? #Ibeere #Yoruba #learnyoruba #speakyoruba #InternationalMotherTongueDay #MotherLanguage #MotherTongueDay https://t.co/9SqkKL4izX | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àkójọpọ̀ àwọn ènìyàn ní nàìjíríà àti lẹ́hìn odi tí wọ́n ń sọ èdè yorùbá ni àwa jẹ́ | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ọmọ Yorùbá àtàtà, #ibeere ti yá o! K'á wo ẹni tí yó fakọyọ. #Ibeere #Ibeere | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
wọn pè yín lólè ẹ tún ń gbomo ẹran jo | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Òfúútù fẹ́ẹ́tẹ̀, áásà tí kò ní kánún.. . Ẹ̀FÚNSETÁN ANÍWÚRÀ jẹ́ àfihàn ìṣe ìmẹ́lẹ́ àti ọ̀nà ìgbà sọ ìtàn tí ó dun’ni jọjọ | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Eje ki a wole adura fun Diziani Aya Madueke omo Alison. Arun yi o gbudo gbe owo mekunu mi bi ti ogagun ologbe Abacha | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Wọ́n ń dàgbà sókè lọ́nà tí ó yára.. . Ààyè wá fún àtúnṣe síi, ṣùgbọ́n ẹ KÚ ișẹ́. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
kí ni ẹyẹ òwìwí ń wá nínú ìpàdé ìgbìmọ̀ ìjọba tanzania | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn kókó-ọ̀rọ̀ tí ó wà nínú Swallow yóò jẹ́ kí ẹnikẹ́ni kígbe - òṣì, ìfipábánilòpọ̀ ìbálópọ̀, ìṣòwo ogun olóró, ìbàjẹ́ ẹ̀tọ́ - ṣùgbọ́n fíìmu náà àti gbogbo àwọn ohun kíkọ jẹ́ aláìlérò àti àìbìkítà. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ọlọ́run Ọba mojúbà o. Ènìà mo kí yín o. #ekaaro | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kí l'ọkùnrin ṣe t'óbìrin ò lè ṣe? #OjoOmobirin | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ibi ọ̀rọ̀ lórí #superstition èèbó ìjàpá ọlọ́gbọ́n àrékérekè ni mò ń bá bọ̀. #Superstition | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user @user Emi na ma d'ara po pelu yin lati #Tweetyoruba niyen. Iru awon nkan bayi ni mo ma'n gbadun lati se. Oya ka lo! | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
A jẹ́ pé bí ng bá ṣe nwí rere ni kí ng máa wí. Bí ng bá ṣe nsọ rere ni kí ng máa sọ. Àṣẹ ni t'Èdùmàrè. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ti a ba ni ki a di oju ki eni buruku koja..... #yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo bi ọ́, ta ni ọ́? #EdeAbinibi #Yoruba #MotherLanguageDay | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Kíni ti Ẹ̀yọ̀ ti ṣe jẹ́ nílùú Èkó Arómirẹ́? Ta ni Adímú? O fẹ́ gbọ́ kúlẹ̀ kúlẹ̀ ọ̀rọ̀? F'ara bálẹ̀, máa bá mi bọ̀. #EyoOrisa #Yoruba # Lagos | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
òwe proverb san là ń rìn ajé ní ń mú ni pẹ kọrọ translation one normally walks straight and upright it is money that makes one cut corners kí èèyàn ṣesọ ohun tó yẹ kó ṣesọ kó yé dẹ́gbẹ̀ kiri one should go straight to the point and stop cutting corners | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ̀yin tèmi, a kú àmójúbà ọdún tuntun o. #happynewyear #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Adìẹ KFC kò dùn mọ́n! https://t.co/pTdEMiv6hb https://t.co/sbWlaYcxPd | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Lọ́sàn-án ganrín-ganrín òní, n ó máa bu omi ẹ̀rọ̀ sí ohun tó le nípa ọ̀pá Ọ̀rànmíyàn. Ẹ máa bá mi bọ̀. #Oranyan #AlayeOro #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Mo ti n tele eyin naa e se o a dupe dupe | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
tó arọ̀ á rọ̀ mọ | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
...tí mo bá tún ayé wa gan-an òun ni màá ṣe. #Ogboni #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Mo kí gbogbo èyàn wa l'ókè òkun àti lẹ́hìn odi gbogbo. Ẹkú àìgbàgbé ilé o. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: #FridayIdioms #YorùbáIdiom:⠀ """"""""Kúndùn"""""""" Kí ni ẹ̀yin kúndùn? (what do you like?) #learnyoruba #yorubaforbeginners #Like… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ààrẹ ọ̀nà kakaǹfò méjì lásìkò kan àwọn ẹni méjì náà ni tóyèjẹ àti ẹdun gbọ̀ngán | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
... Ojumo Iree, Ayo ati Alafiya nii Oni yio jee fun gbogbo waa ...! #Yoruba Dun Nii Ede. | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ó ku ọjọ́ méjìlà fún ìdìbò ìpínlẹ̀ wò ó má gbàgbàkugbà ohun tí kò tó nǹkan pàrọ ọdún mẹ́rin | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ìyá odó òun ọmọ rẹ̀ kò ní ìjà àgbẹ̀ ló díjà sílẹ̀ fún wọn ọmọ odó kì í na ìyá ẹ̀ lásán | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Eyin( Palm kennel) RT @user: Oúnjẹ ni ìkẹ̀tẹ́. Àmọ́, kí la fi ṣe é? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
aremu okikiola ebora owu baba oooo distinguish minister naa kijo mole god bless the race | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ti gba agbara lowo oti gbe fun wan gbe oye awodi le gbenga daniels lowo wan ran ni ise omo toyi o gbon pasiparo ti wan fe fi yo ni igba keji aare lati gbe fun peter obi igi ganganran ma guni loju efun ra o | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Èsì àbájáde àwọn ìfẹsẹ̀wọnsè ti ìdíje #NPFL21 ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ṣé ìwọ náà ní ìfẹ́ sí eré bọ́ọ̀lù-aláfẹsẹ̀gbá? |#TuleChallenge #level5 #ElcheRealMadrid #top4of2020 #wednesdaythought #Buhari #NEWLIV #Yoruba #Tule #petrolprice #notgoingout #NP #thursdaymorning https://t.co/z0DDI81Duf | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Gbogbo àkàṣù kọ́ ló ń fojú kan Ẹ̀fọ́, gbogbo ọmọ ọba kọ́ ló ń dádé"""". Translation: """"Not every morsel gets to meet the vegetable; not all princes get crowned"""". Lesson: It takes being extraordinary to be chosen. #extraordinary #wisesayings #owe #yorubalessons #yoruba https://t.co/MfNZDdu80H | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
16. Èwo nínú àwọn ọba Èkó wọ̀nyí ni ẹni àkọ́kọ́ tí a ó ṣe eré Àdámú-Òrìṣà fún? A. Àdó B. Ológunkúteré D. Akítóyè #Ibeere #Yoruba #Eyo | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
oruko temi ni abiola omo shabi omo bibi ilu eko epe ni awa ti wa won bi mi si ebute metta | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Àìlóye l'ó ń ṣe gbogbo wọn, àmọ́ wọ́n gbàgbé wípé ẹnìkan kì í pa ohùn mọ́ agogo lẹ́nu. Ète wọn ni láti gba ohùn wa, nítorí ọ̀kan gbòógì nínú ohùn ọmọ Nàìjíríà ni @user jẹ́. Àbá nikán ń dá l'ọ̀rọ̀ wọn. | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nínú eré wo ni fọ́nrán yìí wà. #TundeKelani #Yoruba #Nàìjíríà #Ibile #Saworoide #ÈdèYorùbárẹwà @user Birmingham, United Kingdom https://t.co/MYc7JrRgCd | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user Loju temi, Iseda/Eda jé eniyan tabi eranko (Creatures). Awon Igi, Ewebe, Apata - ohun ti Olorun da ni won (Crea… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
♫ Ìnàkí ń ké, Àlàó ń sá lọ, ìròbó ń yọ ní ìdíi bàbá ẹlẹ́mu ♫ | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bí a bá ní àsèdà ọbẹ̀ ni ó ń jẹ, kí ni a fẹ́ sọ? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Aja to ba maa sonu, koni gbo fere #ode.... (#Yoruba) https://t.co/UUiIuwWewa | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: @user. Laye ode oni aya o ji ki oko mo oo ki Olorun gba ni ni oo | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ẹ káàsán o, ẹ̀yin èèyàn wa. Ẹ bá wa parí òwe yìí. 😊😄🤔🤔 • #YorubaCulture #Yoruba #Yorubawedding #nigerians #Yorubademons #Yorubamen #Yorubaparty #Yorubamusic #Yorubacouple #yorubaboys #Yorubalanguage #Yorubareligion https://t.co/NxFqmwkPlF | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Báyìí ni àwọn èkúté náà ṣe lọ, kò bá sí ẹni tí yóò sin àjàó. #Alo #Ajao | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Inú ń bí mi gidigidi. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
agbára ipò kakanfò aláàfin aólẹ̀ bínú ṣùgbọ́n kò bá àfọ̀njá wí wípé ó fi agbára gba ipò kakanfò èyí mú kí àfọ̀njá di ọ̀tá aólẹ̀ àkọ́kọ́ baṣọ̀run àti aólẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sií ní gbọ́nmi omi ò tó nígbà tí àwọn ọmọ baṣọ̀run digun lọ kó ọjà oníṣòwò haúsá tí | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ọ̀pọ̀lọpọ̀ ère wọ̀nyìí ni a pàdánù sí ọwọ́ èèbó amúnisìn | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user Ọ̀rẹ mi àtàtà. Báwo ni òtútù? Ṣé ẹ ti kó gbogbo yìnyín tó rọ̀ sí iwájú ilé kúrò àbí? :) | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
alanu ni oluwa oba ti ng se anu fun eda fi anu wa mi ri loni | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Alẹ́ tí lẹ́, mó fẹ́ f'ọmọ ayò fún ayò n temi. À á jí l'ayọ̀ làgbàrà ònibúọ̀rẹ #IBADAN #Akure #Ijebu #Abeokuta #Kwara #ileIfe #Ilorin | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Bẹ̀rẹ̀ láti ogúnjọ́ oṣù Ẹrẹ́nà títí di òpin ọdún-un 2019, àwọn ajàfẹ́tọ̀ọ́ èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀ ní orí ẹ̀rọ ayárabíàṣá á máa ṣe… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Ohun ayọ̀ ni láti tweet ni édé abínibí. Ọjó̩ ayọ̀ ni ọjó̩ ònì #TweetinYoruba #TweetinYorubaDay | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ jọ̀wọ́ kí lọ́ ń ṣe ní náà | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Igi Akoko, Igi iroko >RT @user: Igi igbó ni ọ̀mọ̀n, afàrà, sọ igi mìíràn méjì tí o mọ̀n? #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""@user: """"""""@user: Ojúmọ́ ire o. Ayọ̀ àti ìfọ̀kànbalẹ̀ ni fún gbogbo wa lọ́jọ́ òní.""""""""Ojúmọ́ 're ni o #ekaaaro"""""""" Amin. O… | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bí o kò bá ní ìgbàgbọ́ nínú ara rẹ, báwo ni ẹlòmíì ṣe máa nígbàgbọ́ nínú rẹ?"""" - Deion Sanders #TranslatedQuotes #AnyQuoteInYoruba #RandomQuotes #RandomThoughts #Quotes #YorubaTranslator #IyaYoruba https://t.co/89D8ClwqSt | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
àwọn olórí burúkú náà kò da ẹran gba igbó àfi ibi oko tí ẹniẹlẹ́ni tí fi gbogbo agbára àti àkókò ṣe | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
B) Òbu. Ohun èlò tí àwọn aláṣetì fi ń se ọbẹ̀ kí a tó mọ iyọ̀. Saltpeter ni ẹ̀ ń pè é lédèe Gẹ̀ẹ́sì. | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Bi iná ba ńjó lóko, màjàlá a ṣe òfófó. / When a farm goes aflame, the flakes (fly home to) bear the tale. [Nothing ca… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
òjò ọjọ́ ajé ọ̀pọ̀ ìbùkún + ire jáǹtìrẹrẹ + ọọrẹ kànkà | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
.@user pelu gbo gbo giran giran yin, ewo bi ero se ya wo @user ni Ipinle @user efara bale! http://t.co/V9HPjqsIe5 | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
todays yoruba motivation ma gberu eleru sori ko o wa fa tire lowotake charge of your own life abo oro ayaworan mi | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
tí mo bá sẹgẹdẹrẹ́ nínúu rẹ̀ mo ṣe ohun gbogbo tí ẹ ní kí n ṣe síbẹ̀ pàbo ló já sí nípa ti òfin tí ìjọba fi de ìlò náà ẹ ò rí nǹkankan ṣe sí i kí wá ló dé tí ẹ fi ń pe ara yín ní ajàfẹ́tọ̀ọ́ òǹràjà bí ẹ ò bá lè gbè wá lẹ́yìn | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Nkò wo gbogbo ìranù yíí.. . Kò yẹ fún ìgbóríyìn rárá,. . Ìranù láti ilè aláwò dúdú tí kò ní àkójopò àwọn òṣèré. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
A kú ọdún tuntun, àṣèyíṣàmọ́dún @user @user | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Omo to ni baba oun o mo obe se itan bi won se le iya e lo lo fee gbo. #funny #YorubaProverbs | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
oke talagbara gun tomi hele oun lomo lorun gun to tun pada wa dupegbogbo oke isoro to wa niwaju wa nio di petele | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ gba àwọn àbá mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yìí kí ẹ sà á bí oògùn kí ẹ mú u lò ire o | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
A ò ní ṣe é TÌ, a ò ní di ÀWÁTÌ t'ilé t'ẹbí t'ọ̀rẹ́ t'ará, ojú ò sì ní í TÌ wá lọ́lá ònìí tí í ṣe ọjọ́ ẸTÌ. #Iwure #Yoruba #Eti #Friday | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Bù fún mi kí n bù fún ọ, ní ọ̀pọ̀lọ́;kọ̀nkọ̀;àkèré ń ké nísàlẹ̀ odò, ọ̀wọ̀ díẹ̀díẹ̀ lara ń fẹ́. #idahunsiIbeere140318 #Owe #Yoruba https://t.co/ofg939itDz | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
lẹ́ẹ̀kansi àti lẹ́ẹ̀kansi ìrẹ́jẹ ìrẹ́jẹ | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Ìdáhùn sí ìbéèrè ìrọ̀lẹ́ àná. #idahun #Ibeere #Yoruba | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Àwọn ẹhànnà tan 'ná, wọ́n sì pa á padà. Òṣì ọrùn! | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Reposted from @user Hello fam, let's have some fun and to all my Saki people, gather here, """"""""ẹ wá fi etí gbé ìyàwó ọ̀rọ̀."""""""" saki.finest mufutau_natalia . . #asa #yoruba_pikin #yoruba_pikin👑 #ede #yoruba #saki… https://t.co/jcoA6GqSDT | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ jẹ́ ká ṣe pẹ̀lẹ́ nínú oṣù agẹmọ yìí ó a kò ní sìṣe láṣẹ èdùmàrè youtube | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
3. Rántí wípé, ẹní bá fẹ́ jẹ oyin inú àpáta ò gbọdọ̀ wo ẹnu àáké. Ìwọ ṣá ma ṣe ohun o mọ̀ ọ́ ṣe lọ, ire ń bọ̀ níkòpẹ́. #Abameta | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Eré tó dára . . Eré tó láti wò láìsí ìjìnlẹ̀ kankan. Kò jinlẹ̀ béèsìni ó panílèrín láìrò | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
a compilation of some nollywood yorùbá eulogy scenes aláàfin ṣàǹgó being eulogized on his coronation day as the aláàfin ọ̀yọ́ àkójọpọ̀ àwọn ibi tí wọ́n ti gbé kí oríkì nínu eré sinimá akéwì ọba ń ki aláàfin ṣàǹgó ní ọjọ́ tí wọ́n fi jẹ ọba source sango movie | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Oun tí Ònkọ̀wé @user kọ ní 2012. """"""""Small Fates"""""""" ní èdè Yorùbá. Ó pèé ní """"""""Kádàrá Kékèké"""""""" https://t.co/eUgmvU1G4Z https:/… | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Ǹjẹ́ o mọ̀ pé méjì méjì ni ẹyẹ-ilé ń bí nígbà'ogbo? Àgbà ní """"""""""""""""t'ọ̀tún t'òsì l'ẹyẹlé fi í kó' re wọlé"""""""""""""""". #Yoruba #Owe http://t.co/nE9vARvJ5k | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
moféràn eré yí . . mà á gbádùn kin ma wó fún ọ̀pọ̀lopọ̀ odún tí ó nbò àti òrò àbásọ tí ó ma ń múwá. . Eré ṣíṣe lo létò láìsí orin aládùn, ó ṣe gbàgbó. Ju gbogbo ẹ lo, eré na dára, ó gba àsìkò mi. | positive | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
a kú ojúmó gbogbo omo kaarò o jíre bí e jé kí a fi owó so owó pò láti gbé àsà ilè wa ní aruge | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
N kò fi bẹ́ẹ̀ gba ti sinimá yìí jàre. | negative | yoruba | NollySenti | movie_review | train |
Adéwálé Àyúbà ní ♫ """"""""obìnrin t'ó bá mọ rírì ọkùnrin, t'ó bá bí'mọ á sì máa gbádùn. """"""""Bí ò bí'mọ á sì máa gbádùn ni ...""""""""♫ #IWD | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Rántí ọmọ ẹni tí ìwọ ń ṣe, rántí ìṣẹ̀ṣeè rẹ. #Yoruba | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
ẹ̀yin tèmi àtàtà mò ńbọ̀ o ṣẹ́ ẹ mọ ìtóri ẹn lọ́nà ẹlẹ́rẹ̀ àdùbí ibẹ̀ layé wá ọmọ yobá ńlọ bẹ̀yá ìyáa mi wò | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
📸 Aiye ti di aiye olaju. Olaju oje ki ori Awa omo Nigeria o pe mo. https://t.co/odQ2zyFd7d | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: """"""""""""""""@user: @user Ẹgbọ́n wa. Ṣé ẹ nlọ sí #smwMotherTongue ?"""""""""""""""" A n pe yin o, lokurin lobirin, lomode lagba, e je ... | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: https://t.co/ddVYLPWB29 •EGBE SHIITE DI EBI RU ORILE EDE SAUDI ARABIA BI OGA YANYAN OLOPA TI NPASE IFOWO OFIN MU WON. •AARE… | negative | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
RT @user: Emi ti mo siwaju won re""""""""@user: Olóríire gbogbo ẹ̀yin dà?"""""""" | positive | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
@user: Lo ka SALTY BROOKS ti @user se ni ana lori storify. tele »: http://t.co/6RyFTlhqda"""" @user"""" bẹ́ẹ̀ ni lọ kà á | neutral | yoruba | AfriSenti | twitter | train |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.