text
stringlengths
3
3.37k
label
stringclasses
3 values
language
stringclasses
3 values
source
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
3 values
split
stringclasses
1 value
RT @user: Mo rerin arintakiti. Awada yi po """"""""@user: @user. Àní kòrókòró ojú mi, owó rèé! Ẹ máa bọ̀ tẹbí-tará. http://t.…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Nítorípé Adáyé sinmi lọ́jọ́ kéje lẹ́yìn tí Ó dá ayé tán, ni Sunday ṣe jẹ́ ọjọ́ ìsinmi. #OjoIsinmi #Itan #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Romper Stomper pèlú Eré lílọ̀ àti àsetán. . . . Fíìmù àsà orí awo tí a gbé jáde ní ọdún séyìn…Tí mo bá féràn Fíìmù Rpmper Stomper, ‘‘This is England,A Clockwork Orange’’… O máa féràn èyí àti ọ̀pọ̀;ọ̀pò tí a ṣe dáadáa…Eré àkọ́kọ́ ṣe àwọn òṣèré máa ń jáde láti è...
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
@user Ó jọ wípé àwọn tí ó ń fẹ́ ìpínyà Nàìjíríà àti ìwàlọ́tọ́ọ̀tọ̀ ẹ̀yà orílẹ̀ èdè yìí ni ó ṣe àwòrán ọ̀hún gẹ́gẹ́ bí owó ìran Yorùbá.
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọ̀run ló mọ ẹni tí ó là.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Òrìṣábùnmi ti di ẹni ẹbọra ń bá jẹun. Òṣèré ńlá mìíràn lọ. Àwa tí a ṣì wà l'áyé láàyè, ẹ jẹ́ kí á pakítí mọ́lẹ̀, kí á tẹ̀ s…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user @user ẹ ti bẹ̀rẹ̀ lálẹ́ yìí, does everything have to do with village people? Well, àwọn ẹlòmíì ni wọ́n ń ṣe ara wọn lóòótọ́. BTW, data is unavoidable for people like me
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user oògùn wo la ò bá lò. Kánàkò ni àbí Olúpòórá? Oògùn ò mà ran àwọn agbófinró ilẹ̀ yí o. #Interpol #GPS #NSA #GCHQ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Òtútù yìí ga o!
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn èèyàn mi ń kanra wípé ẹlẹ́dẹ̀ Trump á bálú jẹ́, àbí ba ayé jẹ́ lóyẹ, pẹ̀lú ète ọ̀bàyéjẹ́ẹ rẹ̀. #Adulawo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìdí abá àkíyèsí ni pé, lóde ònìí ó ti di bárakú, a ti ń pe Òjó ní òjò, p'ojo ní Òjó, à ń pe aṣọ tí a bá mú fún ṣíṣe ní #AsoEbi. #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#FreeEvans? Ori yin kuku ti daru tele! Eyin omo iran kiran. Ani ki wan ti e je ki ewa ma lo, iwa yin o jo iwa eniyan ra ra Iwa eranko gba ni
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Tí a bá gé ilẹ̀ ẹ #Yorùbá kúrò ní Nàìjíríà tó di orílẹ̀èdè Odùduwà, njẹ́ ìjà ò tún ní bẹ́'lẹ̀ pé ẹnìkan l'ẹ̀gbá ẹnìkan n'ìjẹ̀ṣà?
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹkáàárọ̀ o njẹ́ mo ti da omi síwájú óyá kí máa wá tẹlẹ̀ tútù ire níwájú ire lẹ́yìn lágbára ọlọ́run ọba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìṣe + kú + ìṣe = ìṣekúṣe ọmọ + kí + ọmọ = ọmọkọ́mọ ìran ++ ìran = ìrandíran
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user rọ ọmọ Nàìjíríà pé kí a lo ẹ̀rọ alátagbà fún jíjà fún ẹ̀tọ́ lọ́nà tó yẹ #Smwadvocacy http://t.co/7sutsqeTkC
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Toò. Àsùnjí o. Kí Ọlọ́run ṣọ́ wa dàárọ̀ o. #odaaro
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
6. Àṣà ìdábẹ́ ti ṣe díẹ̀ ńlẹ̀ẹ Yorùbá, ta ni ẹni àkọ́kọ́ tí a dá abẹ́ fún? #ibeere #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ifá ní, """"""""Èjìgbèdè gbígbè ni ó gbè mí, a díá fún Ojúorò tí ń lọ ìsàlẹ̀ àbàtà, tí ń lọ rè é kanrílẹ̀ ọmọ ní bíbí."""""""" #BiEyekoSeDiEyele
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Airin jinna lai ri abuke okere,... __RT""""""""@user: Ẹ gbàmí! Ẹja tútù ni àwọn wọ̀nyí ń kó jẹ bí ẹní jẹ̀bà o. http://t.c…
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""@user: @user Ń'torí Ọlọ́hun.. ẹ wo àkàṣù iyán! Toò. Yó gba'bi ire o."""""""" Mo rin erin muse'e.. eseun lopolopo.. ek ...
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ise Destiny Ekaragha "Gone too far" jọ londonu, Naijiria ati Jamaica, ó sì pani lè rìn púpò. ó mú mi sínú aranpo, mo sì rẹ́rìn-ín kárakára títí tí aranpọ náà fi ja. Mo feran ìtàn ère náà tí ó ní ìwọ̀n tí ó yára, pelu orin rẹ tó peni mọ́ra.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
K'á jáwé, k'á wa egbò ilẹ̀ tí yóò pa kòkòrò-àìfojúrí lápa tán, k'á jáwọ́ lápọ̀n tí ò yọ̀. @user #waaw #Antibioticresistance #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọlọ́run á bá àìní wa pàdé. Àmín #TweetYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹgbọ́ o, ṣebí èyàn ẹlẹ́ran-ara náà ni àwọn òṣèlú wa? Wọn a máa s'òòṣà ni? Ìdájọ́ nbọ̀ f'ólúkálukù. #GEJ #Naija
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Fíìmù My Village People jẹ́ èyí tí ó jẹ́ pé á mú ẹ sọ ẹ̀kọ́ ìwà dídára rẹ̀ ẹ nù. Ṣùgbọ́n ó jẹ́ bíi olùtọ́pa ọ̀nà ni bákàn. Lápàapọ̀, Nollywood ò kìí ṣe àwọn ipa oní agbára ìbílẹ̀ dáradára. My Village People ṣe é yàtọ̀ ní ọ̀nà tó dára, ó sì yẹ fún ìgbórí...
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Orí gbé aláwo ire kò mí.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Kò yé @user rárá; wọn ò da mọ̀. #TweetYoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
D’ijú, kí o se bi ẹni kú, ki o le mọ ọ̀rẹ́ ti o fẹ ọ Abi ile aye yi kọ? #YorubaPoem #Yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Eré ńlá. Mo gbádùn bí wọn benu àtẹ́ lú aisedede àwọn ọlọ́rọ̀ àti àwọn alágbára ju kí a mo ṣe ìwàláàyè wọn lógo.
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
RT @user: Ki osi je kin nko ere ijade mi wale Eledua""""""""""""""""@user: Pa àlọ àti ààbòo mi mọ́ Baba""""""""""""""""
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
amin oo ire á je ti wá
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
amìn o ki orí wa joba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
tí wọ́n bá fi ẹ́wàá ẹ wa pa àrọkò sí èèyàn ó túnmọ̀ sí wípé wọ́n ti ń wá ẹni náà kí ó ma bọ̀ ní ìtòsí if they send ten as an encrypted message to someone it means they have been searching for the person so heshe should come around
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ọmọ ìbàdàn kíni sóò èyí ni ìkéde ìgbélárugẹ aṣọ aránṣọ oǹwọṣọyanfandalórí ìtàgé tí yóò wáyé ní
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""Kò sí l'átẹ, Olówó kò rí ọmọ rà, Ibi tí ó mọ, Ní í jẹ́ ọmọ, Ọmọ ẹni kò ṣe ìdí bẹ̀ bẹ̀rẹ̀, Kí á fi ìlẹ̀kẹ̀ sí ti ẹlòmíràn,…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo lọ sílé ìjẹun #Igbo kan láti jẹ ọbẹ̀ ewúro. Ẹnìkan wọlé bá mi, ó sì ní kí wọ́n fún òun ní ọbẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta; olúgbù, ègúsí àti àpọ̀n. Ó ga o!!!
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ogun àmọ̀tẹ́lẹ̀ kìí pa arọ. #TrumpPence16
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bí ọmọdé ń ṣèṣe ọmọdé àgbà á ṣe bí àgbà
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ajé o! Gbé 're ayé mi kòmí lónìí tí í ṣe ọjọ́ Ajé. Kájé o bugbá jẹ, kí n rí tajé ṣe lọ́sẹ̀ yìí. Kájé ó máa báwa gbé títí #Ekaaaro
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ìjọba etíi yín mélòó, kí èdè abínibí jẹ́ baríbakú nílé ìwée wa kí ẹ wa rí ìdàgbàsókè tí ò lẹ́gbẹ́. @user #YesVernacular @user
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
òótọ́ ni wípé rírò ni tèèyàn ṣíṣe jẹ́ ti ọlọ́run bẹ́ẹ̀ àtẹ́lẹwọ́ ẹni kì í tan ni í jẹ yé sùn sọjí ayé ẹ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orin yii dun oooo
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user ẹ kú déédéé àsìkò yìí o, ẹ dákun ó lọ̀rọ̀ kan tí mo fẹ́ bá a yín sọ. Ẹ wo DM. Ẹ ṣeun púpọ̀.
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo n lo sabeokuta mo fe lo to omo Soyinka, osoyinka ooo"""""""" @user ~ Olumo #brymo #Nigeria #Ogun #music #musixmatch #WoleSoyinka #NigerianMusic #Yoruba #Tribe #Weirdmaskman https://t.co/6v6K6t5Kpk
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
HOW WELL DO YOU KNOW YORÙBÁ LAND/ BÁWO NI O ṢE MỌ ILẸ̀ YORÙBÁ SÍ? 1) How many Masquerades do they have in Ìlọrin? 1) Eégún mélòó ni wọ́n ní, ní Ìlọrin?
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Pírí l'olongo ń jí, a kì í bá olókùnrùn ẹyẹ lórí ìtẹ́. Mo jí ire. Elédùmarè mo ṣ'èbà rẹ!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user Ati ore ati ika, kosi iyi to gbe, owun †i abagbin lao ka
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: To ri ina n jo igi tutu gan tewetewe, sebi ojo n gbe eni to m'owe lo...
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Gẹ́gẹ́ bí àpẹẹrẹ: Ọmú-u Fúnmilọ́lá, kì í ṣe ọmú Fúnmilọ́lá. Okó-o Kọ́láwọlé ✔️ Okó Kọ́láwọlé ❌ Bàtà-à mi ✔️ Bàtà mi ❌ Ir…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Omo leyin oya gba IPOLONGO TO KABITI @user: Shey gbogbo Omolehin mi o ni fun mi ni Ipolongo(S/0) abi ...........#Tw ...
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ ti gbà á tán èmi àti enyeama ń jó samba lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ìgboro rio ṣé ẹ̀yin náà ń bọ̀ àbí
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Bẹ́ẹ̀ni o. Aiyé nyí lọ à ntọ̀ọ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Also super special to see and hear #Yoruba. """"""""Abogbo wa ni ọmọ rèẹ nínú èjè àti egungun."""""""" Words to remember. #ChildrenofBloodandBone
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àṣìṣé ni pé òún lọ, àmọ́ ó tún wá kó ènìà mẹ́rìndínlọ́gọ́fà lọ. Ìwà olórí burúkú kọ́ rèé? #GEJ #brazil
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹ ṣeun fún àsìkò yín. Àmọ́, kí ẹ tó lọ, kíni àmọ́ràn tí ẹ lè fún àwọn òǹkọ̀wé àti òǹkàwé ní èdè Yorùbá, bí wọ́n ti lè gbé èdè Yorùbá lárugẹ? Atì wípé, bí àwọn òǹkọ̀wé ṣe lè tún bọ̀ ma kọ̀wé ní Yorùbá, bí ó ti jẹ́ wípé, ọ̀pọ̀ èèyàn kò mọ Yorùbá kà púpọ̀
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
mo fẹ́ràn like láti ma jẹ ẹ̀fọ́ ẹlẹ́gùúsí pẹ̀lú ẹ̀bà tó múrọ̀ọ́ lọ́wọ́ mo nífẹ̀ẹ́ love ọmọbìnrin tó rẹwà kan tí mo pàd
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
...mìíìn kò ní rí i. Kàkà kíyàwó yẹn jẹ́ kó máa lọ bẹ́ẹ̀, níṣe ló lọọ lóyún fẹ́lòmíììn tí yẹn kò tíì kú. Bó ṣe di pé ọkọ ẹ̀ kò lè wá mọ́ nìyẹn. Ìgbà tóbìnrin yẹn fẹ́ẹ́ bímọ lòun náà kú. Kì í ṣe àròsọ rárá, Ìjokò yìí ló ti ṣẹlẹ̀ nígbà náà...
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ kú ọdún Eid-al-Fitri, ẹ̀yin ẹlẹ́sìn Ìsìláàmù. Ẹ̀mí yín tó rí ẹ̀yin oṣù yìí á ṣe bẹ́ẹ̀ lámọ̀dún. Ẹ rántí fi àdírẹ́sì ránṣẹ́ kí a lè wá yọwọ́ ṣíbí o! Ire! #EidAlFitr2019 #Yorùbá #Prayers #RamadanMubarak https://t.co/P1XoQUZ3jn
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ọládàpọ̀ Ọláìítán Ọláònípẹ̀kun: Dagrin ti sọ kí ó t'ó lọ, ó ní """"""""... Ó pay mi kí n kúò ní Nigeria kí n sá lọ sí Abidjan ♫. @user
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ibi ti emi dari wa si laaro yii niyen :-D""""""""@user: @user hmmm,o se owo wasiu ayinde lowuro yii.""""""""
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àkàrà tú sépo
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
bẹ̀rẹ̀ láti ogúnjọ́ oṣù ẹrẹ́nà títí di òpin ọdúnun àwọn ajàfẹ́tọ̀ọ́ èdè ilẹ̀ adúláwọ̀ ní orí ẹ̀rọ ayárabíàṣá á máa ṣe ọ̀ọ̀wẹ̀ láti ṣàkóso aṣàmúlò túwítà
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ìkòkò amọ̀ ní èkìtì ní ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rúndún mọ́kàndínlógún tí wọ́n fi ń gbe omi fún ìlò ojojúmọ́ ìgbàgbọ́ ni wípé omi tí wọ́n fi ń fọ ẹsẹ̀ ìyàwó titun tí ó bá fẹ́ wọ ilé ọkọ rẹ̀ lè wà nínú ìkòkò náà orísun ìmọ̀ yìí
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
nítorí akitiyan jagunjagun lójú ogun ni ọba àtijọ́ kan tí ó gbó tí ó tọ́ fi dá oyè
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Kínni àǹfààní orógbó? A pa á, kò láwẹ́, a bù ú jẹ, ó korò. Igi rẹ̀ ò ṣe é dáná, bẹ́ẹ̀ ewé rẹ̀ kò ṣe é pọ́n ẹ̀kọ ọmọ #orogbo #oroyoruba #yoruba
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ó dọwọ́ọ gbogbo wa @user #Asa #Yoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
òpin oṣù kẹfà mosọ́pẹ́ ng ò bá a lọ orí modúpẹ́ agẹmọ wọlé dé ire ayé mi wọlé dé á á ṣẹ àṣẹ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
a ó rẹ̀ ìwọ gíga ènìà sílẹ̀ a ó sì tẹ̀ orí ìgbéraga ènìà ba olúwa nìkan ṣoṣo li a ó gbé ga lí ọjọ́ náà
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ti a o ba gbagbe oro ana, ao ni ri enikan aa ba sere. Dokita Frederick Fasehun lo so be. Wan ni ki omo Karo Ojire te ote mole fun ilosiwaju
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: """"""""@user, @user, ChemistryWorld: orisi ogun meji fun arun jejere ni won ti gba wo le http://t.co/kWBeCgXh…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Yoòbá bọ̀ ó ní, ogun ní í ṣi ni mú, èpè kì í ṣi ni jà. Tótó ṣe bí òwe o! #OgunIleYoruba #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ gbọ́ kí lẹ ti rí sí ti ìwé àbádòfin ìmúkúrò ìṣẹ̀ṣe ìfọbajẹ àti ètò ìkẹyìn àwọn ìgbá-kejì-òrìṣà tí ó ti jẹ́ kíkà lẹ́rìnmejì nílé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Ògùn? Ṣé kí a pa àṣà ìbílẹ̀ tì, kí a máa lo ìlànà ìgbàlódé fún ètò ìfọbajẹ? #Ogun #Isese #Yoruba https://t.co/6FrjtrqpCZ
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
lẹ́nu ọjọ́ mẹ́ta yìí sánmà á kàn ṣe gùdẹ̀rẹ̀ bí ẹni pé òjó fẹ́ rọ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
èdùmàrè gbére ajé olókun kò mí lóòwúrọ̀ tòní owó tabua àbùbùtán owó tútù tí í dẹ́rù ba àgbàná ni kí o fi ṣe tèmi
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àb'ẹ́ẹ̀ rí i pé nkan ti wá dojúrú báyìí?
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
orí ò mọ ibùsùn ì bá tún ibẹ̀ ṣe láàárọ̀ we do not know our future for certain else we would have prepared for i
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: A kò gbọdọ̀ torí kòkòrò kó sí'ni lójú, ká wá ki igi bọ ojú ọ̀hún. / One shouldn't poke a stick into one's eye simply…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ÒWE / PROVERB Ọbẹ̀ kìí gbé inú àgbà mì Ohun tí a bá fi pamọ́, kò yẹ kí ẹlòmíràn mọ̀ nípa rẹ̀. TRANSLATION A soup does not shake in the stomach of the elder. The art of keeping a secret is very important.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
sì ma ju owó tí wọ́n yá jáde lọ, nígbà tí wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí ní ká èso lóko. Orísun ìmọ̀ yìí: Adebanji Akítóyè, A History of The Yoruba People, Amalion Publishing, Dakar.
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Kú ni àfòmọ́ ìbẹ̀rẹ̀ tí à ń fi sí ìbẹ̀rẹ̀ ìkíni. 'Ẹ' fún ajunilọ, 'o' ni fún sàwáwù ẹni. #oku #ku #ikini #asaikini #Yoruba…
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Oruko mi ni Adegboyega omo Adejorin abi mi ni ilu Kaduna ni oke oya,omo ilu Ibadan ni mi #tweetinyoruba @user @user @user
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Eto Ẹkọ SKALE tio Bẹrẹ lori Coinbase yio fun o ni anfaani lati mo siwaju si nipa netwọọki SKALE. Ka Ayoka yi fun alaye le…
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
#Loriiro #Igbo #Yoruba #lagos Corruption ti hit nation Gbogbowa la n live in desperation Tori 'e n'mo se n drink medication Fun protection against starvation pelucorruption Tori generation yii, a need salvation Through astrong constitution Ninu studio,owo naa l'afi n book session
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Tó ómó ré ki ole fun é ni isimi #TweetinYoruba
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Onise iyanu,(Miracle worker) Onise ara,(Wonderful) Onise nla,(Great God) Mimo, Mimo, Mimo,(Holy! Holy! Holy) Oba t’o ninu mimo,(Righteous God) Oba alaya funfun,(Immaculate God) Not gonna lie.. praising God in #Yoruba sounds a lot more fun 😄 #CelestialWeekly #ProudlyCelestian
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
@user Ẹkáàárọ̀ o. Ire ni o. Àti ẹ̀yin náà!
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Ẹ kú ọjọ́ Ẹtì Rere o. Mo gbà á láàdúrà pé gbogbo ohun burúkú ayée wa yóò di rere. #GoodFriday #OjoEtiRere
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Lára Irúnmọlẹ̀ mẹ́rìndínlógún t'ó rọ̀ sí Otù Ifẹ̀ ni Ògún àkọ́kọ́ í ṣe, ènìyàn bíi tèmi tìrẹ̀ ni Ògún Ọ̀yọ́, t'ó ṣ'ìkejì. #OsuOgun #Yoruba
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
wọ́n á ní ọjọ́ a bá kú là á di ère ǹjẹ́ ó ní ìdí tí àwọn àgbà fi pa òwe bẹ́ẹ̀ ndan ọ̀rọ̀ ń bọ̀ lórí ẹ̀ láìpẹ́
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Oògun jẹ̀díjẹ̀dí, ìròbo yíyọ àti ìgbẹ́ ẹlẹ́jẹ̀. Èso awòròso méjìlá. Iyọ̀ òyìbó (sugar). Àdí ẹ̀yan. Ṣíbí kan lọ́jọ́ mẹ́tamẹ́ta. #Yoruba https://t.co/ZinRtTFfrx
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Àwọn ọ̀rọ̀ tí ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àṣì wo lo mọ̀? #Asi #Ibeere #YorubaQnA
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: Gbogbo shakara awon oloshelu wa o koja Naijiriya RT @user: Fáàrí ọ̀bọ ò ju'nú ìgbẹ́ lọ. #owe
negative
yoruba
AfriSenti
twitter
train
òrìṣà ọdẹ jagunjagun ọlọ́pàá agbófinró adájọ́ àti oníṣẹ́ bẹ́ẹ̀ ni òṣóòsì
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
ẹ̀gbọ́ ẹ kú ọjọ́ ìbí o ire ńlá ńlá á jẹ́ ti yín lọ́láa èdùmàrè ìsẹ
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
àti iyin ekiti o àti ado ekiti o ti olúwa nilẹ̀
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
Mo féràn Eré náà. . O bẹ̀rẹ̀ pèlú àíyára ṣùgbọ́n ó dìde kíákíá! . . Àìgbọdọ̀ máwò ó ni
positive
yoruba
NollySenti
movie_review
train
Molten jẹ́ kí ẹgbẹ́ ó mọ orísun omi odò Senegal, Gambia. #Nigbatiwonde #Adu
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train
RT @user: @user e kaaro o. Owo ero inu ojo la wa sun nibi l'Akure. Ojumo 're o
positive
yoruba
AfriSenti
twitter
train
L'ókè ọya níbí, orin òyìnbó ni àwon ẹgbẹ́ akórin ṣọ́ọ̀ṣì wa ma n kọ bíi ọ̀pẹ́ẹ̀rẹ̀ ṣùgbón, a ṣe ìsìn orin kan níjọ́sí ,wọ́n bá pe onílù kan wa. Okùnrin yìí ma gbá ìlù oooo, Háà, àjẹbí lógbọdọ̀ jẹ́,ọmọ àyàn tómọ èdè ìlù ni #Yorùbá
neutral
yoruba
AfriSenti
twitter
train