raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
liu yandong liu yandong tí wọ́n bí ní ọjọ́ méjìlélógún oṣù kọkànlá ọdún 1945 nẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè china tí ó ti fìgbà kan tẹ́lẹ̀ rí jẹ́ igbákejì olórí orílẹ̀-èdè china tẹ́lẹ̀ rí ó sì jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú politburo of the communist party of china láàrín ọdún 2007 sí 2017 ó sì tún jẹ́ àbójútó ní ìpínlẹ̀ kan ní orílẹ... |
list of national parks of china wọ́n ṣe ìfilọ́lẹ̀ ibùdó ìgbafẹ́ ti ìjọba apapọ̀ ní orílẹ̀-èdè china ní ọdún 2013 níbi ìpàdé plenary session of the 18th central committee of the communist party of china ẹlèkẹta iru rẹ̀ nígbà tí ó di ọdún 2016 wọ́n ṣe agbékalẹ̀ ibùdó ìgbafẹ́ eti omi tàbí odò three-river-source national p... |
chinees tea |
àtòjọ orúkọ àwọn akéwì lédè china wikipedia list article èyí ni àtòjọ orúkọ àwọn akéwì lédè china |
àtòjọ àwọn oǹkọ̀wé-bìnrin ọmọ china wikipedia list article àwọn wọ̀nyí ni àtòjọ àwọn oǹkọ̀wé-bìnrin ọmọ china d oǹkọ̀wé ìtàn àròsọ |
velekete slave market |
ìyálóde ìyálóde jẹ́ obìnrin onípò gíga nínú ọ̀pọ̀ àwọn ìlú ìbílẹ̀ yorùbá lóde òní àwọn ọba ló ń fi obìnrin joyè ìyálóde àmọ́ lọ́dún 2002 njoku ṣàlàyé pé láyé àtijọ́ nílẹ̀ yorùbá ìlànà ìyannisípò gẹ́gẹ́ bí ìyálóde kò jẹ mọ́ ìpinnu ọba kàkà bẹ́ẹ̀ yálà a ó fi obìnrin joyè ìyálóde tàbí bẹ́ẹ̀ kọ́ dá lórí àṣeyọrí àti ìkópa n... |
olumide makanjuola a bí olumide makanjuọla ní ọjọ́ keje oṣù kẹfà ọdún ó jẹ ọmọ bibi orilẹ-ede naijiria o si tun jẹ a ja fun ẹtọ ọmọniyan on s'ọtan ni bakanna lo si je agbẹjọro fun agbekalẹ ti a n pe ni lgbtqi ati gbajugbaja olokoowo oun ni oludari agba fun the initiative for equal rights tiers ile iṣẹ yii lo n ja fun i... |
ògì |
pamela adie nigerian lgbt rights activist and filmmaker pamela adie jẹ́ ònkàtàn olùbá ọ̀pọ̀ èrò sọ̀rọ̀ ato ajìjàn-n-gbara fún ẹ̀tọ́ àwọn lgbt ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà pamela di ìlú mọ̀ọ́ká pẹ̀lú akitiyan rẹ̀ lórí ẹ̀tọ́ awọ lgbtq ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà iṣẹ́ ìwádí rẹ̀ ni ó dá lé lgbt rights in nigeria lọ́rísiríṣi lára ìwé ... |
james brown internet personality james obialor tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí james brown ni wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kejì ọdún 1999 jẹ́ oníṣẹ́ orí ẹ̀rọ ayélujára oníjó àti cross dresser tí ó di gbajú-gbajà ní ọdún 2018 látàrí fọ́nrán kan tí ó di tọ́rọ́ fọ́nkalé lórí ẹ̀rọ ayélujára tí wọ́n sọ wípé they did not caught m... |
bobrisky bobrisky jẹ́ ènìyàn pàtàkì lórí intanẹẹti ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó jẹ́ obìnrin tí a tún mọ̀ sí trans woman ní ilẹ̀ nàìjíríà orílẹ̀-èdè tí kò ní àwọn ètò fún lgbt ó tún jẹ́ eni tí ó ma ń sábàá fi arahàn lórí ẹ̀rọ ayélujára ti àwùjọ media tí wọ́n ǹ pé ní ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ bobrisky okuneye idris olare... |
temmie ovwasa nigerian alt-rb singer temmie ovwasa tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlógúnọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 1996 ni gbogbo ènìyàn mọ́ sí ybnl princess ni ó jẹ́ olórin olùkọrin àti òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó sì ń akọrin pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ agbórin-jáde ybnl nation nígbà tí ó fọwọ́ sí ìwé àdéhùn pẹ̀lú wọn ní inú oṣù k... |
akudo oguaghamba akudo oguaghamba ni ó jẹ́ a jà fẹ́tọ́ ọmọnìyàn olùkọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ti kọ ìwé ìwádí nípa ẹ̀tọ́ àwọn lgbtq òun ni olùdásílẹ̀ àjọ women's health and equal rights wher ó sì tún jẹ́ ọ̀kan kan ṣoṣo lára àwọn olùdásílẹ̀ pan-african ilga international lesbian gay bisexual trans and intersex ass... |
seyi adebanjo seyi adebanjo ni ó jẹ́ genderfluid queer mfa media artist tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó sì ti fi ìlú new york city ṣe ibùgbé báyí ni ó ni lọ́kàn láti ma ṣe ipò lòó fún àwọn ìpèníjà tí ó ń dojú ke ẹ̀yà adámọ́ àjọ ati abo tàbí ìbálòpọ̀ nípa yíya àwòrán ṣíṣe fọ́nrá tabí eré àgbéléwò àti àwọn àpilẹ̀kọ... |
uyaiedu ikpe-etim uyaiedu ikpe-etim tí wọ́n bí ní ọdún 1989 jẹ́ olùgbéré-jáde àti ònkọtàn ọmọ orílẹ̀-èdè *nàìjíríà tí ó kéde fún ẹ̀tọ́ àwọn lgbt gẹ́gẹ́ bí àwọn ènìyàn kan tí wọ́n ń fi ẹ̀tọ́ wọ jẹ wọ́n níyà ní inú ọdún 2020 ilé-iṣẹ́ bbc fi orúkọ rẹ̀ sí ara àwọn ènìyàn ọgbàọ́rùn un obìnrin fún ọdún 2020 100 women of the ... |
akínwùnmí àḿbòdé |
ayo fayose |
ayọ̀ fáyóṣé |
david gentleman david william gentleman rdi jẹ́ òsèré gẹ̀ẹ́sì tí abí ní ọjọ́ kọkànlá osù kẹta ọdún 1930 ó kẹ́kọ̀ọ́ àpèjúwe ní ilé ẹ̀kọ́ royal college of art lábé àkóso àti john nash o kẹkọọ apejuwe ni royal college of art labẹ edward bawden ati john nash o ti ṣiṣẹ ni awọ-omi lithography ati kikọ igi ni awọn iwọn ti o w... |
moji solar-wilson moji solar-wilson tí wọ́n bí ní ọdún 1968 ni ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ìjerò èkìtì ní ìpínlẹ̀ èkìtì jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè a nàìjíríà àmọ́ tí ó fi ilú wngland ṣe ibùgbé jẹ́ alàgàta láàrín broker òntà àti ònrà ó ń bani ralé ralẹ̀ bẹ́ẹ̀ ni ó jẹ́ ọ̀kan lára awọn lgbtqia+ a jà fẹ́tọ́ ọmọnìyàn aláríwísí àwùjọ àti olù... |
cyril nri cyril ikechukwu nri tí wọ́n bí ní ọjọ́ kaẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 1961 jẹ́ british-nigerian òṣèré ònkọ̀tàn àti adarí eré tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí adam okaro nínú eré àtìgbà-dégbà orí amóhù-máwòrán the bill ibẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ bàbá ati ìyá nri jẹ́ ọmọ ẹ̀yà igbo tí wọ́n sa àsálà fún ẹ̀mí wọn ní àsìkò ogun abẹ́lé ... |
ayodele olofintuade ayọdele ọlọfintuade jẹ́ òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà oníròyìn àti ẹ̀yà abo ó ti ṣe àfihàn ara rẹ̀ gẹgẹ bíi ẹni tí kii ṣe alákọméjì ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà orílẹ̀-èdè tí ó ṣe ìlòdì sì lgbtq ìgbésí ayé e rẹ̀ a bí ayọdele ọlọfintuade ní ìlú ìbàdàn orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 1970 ní àárín eko ibadan ... |
lagos state model college kankon lagos state senior model college kankon je oun ini ijoba ilu eko to je ile eko giga ni opopona owode-apa ni badagry lga lagos state o ti da ni ọdun 1988 lakoko iṣakoso ologun ti rear admiral mike akhigbe rtd itan lsmc kankon jẹ ọkan ninu awọn kọlẹji awoṣe marun ti a ṣeto ni ọkọọkan ninu... |
victoria aguiyi-ironsi victoria nwanyiocha aguyi-ironsi 21 oṣu kọkanla ọdun 1923-23 oṣu kẹjọ ọdun 2021 ni iyaafin akọkọ ti nigeria keji lati ọjọ 16 oṣu kini ọdun 1966 si 29 oṣu keje 1966 o jẹ opo ti general johnson aguiyi-ironsi ti o jẹ olori ologun akọkọ ti orilẹ-ede naijiria igbesiaye arabinrin naa wa lati ohokobo af... |
ìlárá-mọ̀kín ìlárá-mọ̀kín jẹ́ ìlú ẹ̀yà èkìtì tó wa nínú àgbègbè-ìjọba ní ìpínlẹ̀ òǹdó ìlárá-mọ̀kín súnmọ́ àwọn ìlú bí àkúrẹ́ ìpogun ìkọta èró ìgbàrà-okè àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ́ wọ́n sọ ẹkà-èdè yorùbá tó jẹ́ èdè èkìtì |
chike frankie edozien chiké frankie edozien jẹ́ ònkọ̀wé àti oníṣẹ́ ìròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ati amẹ́ríkà òun ni adarí àgbà fún new york university accra òun náà sì tún ni olùdarí fún new york university journalism orisirisi àpilẹ̀kọ ni ó ma ń ke tí ó sì ń gbé jáde nínú àwọn ìwé-ìròyìnrẹ̀ òun ni ó kọ ìwé lives of ... |
aaliyah brown sprinter aaliyah brown tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kínní ọdún 1995 jẹ́ asáré orí ọ̀dan ayára pá sprinter ọmọ orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà ó kópa nínú ìdíje women's 4 × 100 metres relay at the 2017 world championships in athletics |
sweets for the sweet sweets for the sweet ni ó jẹ́ orin tí oní fèrè kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ harry sweets edison tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 1964 lábẹ́ ilé-iṣẹ́ agbórinjáde sue |
richard akuson richard akuson tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndílọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 1993 jẹ́ agbẹjọ́rò ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ajà fún ẹ̀tọ́ lórí lgbtq òǹkọ̀wé olóòtú àti olùdásílẹ̀ ìwé ìròyìn tí wọ́n ǹ pé a nasty boy èyí tíí ṣe ìwé àtẹ̀jáde äkọ́kọ́ lórí lgbtq+ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọdún 2019 richard wà lára forbes áfíríkà... |
mandy la candy mandy la candy jẹ́ ọkùnrin tí ó yí ara rẹ̀ padà sí obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè is a canada tí ó ń fi orílẹ̀-èdè nàìjíríà ṣe ibùgbé mandy ni wọ́n mọ̀ sí okwudili ṣáájú kí ó tó yí ara rẹ̀ padà sí obìnrin ní ọdún 2016 ó gbé àwòrán ara rẹ̀ tí òun ati ìyàwó olórí orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà tẹ́lẹ̀ ìyẹn melania trump's ìyẹ... |
rizi timane rizi xavier timane ni ó jẹ́ olórin mínísítàònkọ̀wé ẹni tí ó yí ara rẹ̀ padà sí ọkùnrin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ibẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí timane ní ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́jọ orísiríṣi ìdàamú ni ó bá padé ní ọwọ́ awọn òbí àti olùṣọ́ agùtàn sọ́ọ̀ṣì wọn nígbà tí wọ́n ṣàkíy... |
nnanna ikpo nnanna ikpo jẹ́ ònkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó di gbajúmọ́ fún ìwé rẹ̀ tí ó pe akòrí rẹ̀ ní fimí sílẹ̀ forever ní ọdún 2017 wọ́n yan ìwé yí fún àmì-ẹ̀yẹ lambda literary award níbi gay fiction níbi ìdíje 30th lambda literary awards ní ọdún 2018 |
logan february logan february tí wọ́n bí ní ọdún 1999 jẹ́ akéwì alágbéyẹ̀wò orin alápilẹ̀kọ akọrin olórin ati ajìjàngbara fún àwọn lgbtq ibẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí logan february ní ìpínlẹ̀ anámbra ní ọjọ́ kẹ̀tàlélógún oṣù kẹrin ọdún 1999 ó sì dàgbà sí ìlú ìbàdàn ó kẹ́kọ́ nípa psychology ní ilé-ẹ̀kọ́ yunifásítì ìlú ìbàdàn... |
william rashidi william rashidi jẹ́ ajìjàngbara fún àwọn ọmọ egbẹ́ lgbtq ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí wọ́n ń lọ́wọ́ nínú ìbálòpọ̀ láàrin akọ sí akọ àti abo sí abo ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ ìgbìmọ̀ tí ó ń darí ilé ṣiṣi fún ìlera àti àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn òun tún ni olùdarí ti equality triangle initiative èyí tí ó fìdíkalẹ̀ sí ipinle ... |
vincent desmond vincent desmondjẹ́ oníṣẹ́ ìròyìn tí ó jọ mọ́ àṣà ònkọ̀tàn olóòtú ati olùpolongo ẹ̀tọ́ àwọn lgbtq tí ó fi ìpínlẹ̀ èkó ṣe ibùgbé ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni olóòtú àgbà fún ìwé-ìròyìn olóṣooṣù nípa oge ṣíṣe kan tí wọ́n pe ní a nasty boy tí ọ̀gbẹ́ni richard akuson tí ó jẹ́ oníṣẹ́ ìròyìn àti amòfin da síl... |
ezra olubi ezra olubi tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kọkànlá ọdún 1986 jẹ́ olùdásílẹ̀ òwò ara ẹni onímọ̀ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ software developer olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ paystack àti ajàfẹ́tọ́ born 12 november 1986 ètò ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ rẹ̀ ezra kàwé jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ babcock university nínú ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀rọ kọmpútà ní ọdún 2006 ... |
shola akinlade ṣọlá akínlàdé jẹ́ onímọ̀ nípa software ati ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ paystack ètò ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ rẹ̀ ṣọlá lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama st gregory's college tí ó sì jáde ìwé mẹ́wá jáde ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ babcock university níbi tí ó ti lọ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ kọ̀mpútà tí ó sì jáde níbẹ̀ ní ọdún 2006 ó bẹ... |
tiwalola olanubi tiwalola olanubi jnr tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdílọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1988 jẹ́ olókowò ara ẹni lórí oúnjẹ oníṣẹ́ ìmọ̀ ẹ̀rọ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni olùdásílẹ̀ ilé-iṣ́ẹ́ dotts media house èyí tí ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ilé-iṣẹ́ tí ó lààmì-laaka ní ilẹ̀ adúláwọ̀ nípa digital marketing òun náà tún ni o... |
affiliate marketing titaja alafaramo jẹ iru /https//enwikipediaorg/wiki/performance-based20advertising titaja ti o da lori iṣẹ ṣiṣe ninu eyiti iṣowo ṣe ere ọkan tabi diẹ ẹ sii awọn alajọṣepọ fun alejo kọọkan tabi alabara ti o mu nipasẹ awọn akitiyan /https//enwikipediaorg/wiki/affiliate20commerce titaja alafaramo /http... |
pay-per-click pay-per-click ppc jẹ awoṣe ipolowo intanẹẹti ti a lo lati wakọ ijabọ si awọn oju opo wẹẹbu ninu eyiti olupolowo kan n sanwo fun akede kan ni deede ẹrọ wiwa oniwun oju opo wẹẹbu tabi nẹtiwọọki ti awọn oju opo wẹẹbu nigbati ipolowo ba tẹ isanwo-fun-tẹ ni apapọ pẹlu awọn ẹrọ wiwa akọkọ-ipele bii awọn ipolowo... |
a nasty boy a nasty boy a nasty boy jẹ́ ìwé ìròyìn àkọ́kọ́ kan tí wọ́n da sílẹ̀ ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kejì ọdún 2017 tí ó da lè ọ̀tọ̀ nípa àwọn lgbtq ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìwé yí ni ó ń sọ nípa ìtàn ìrírí ati àkòrí ọ̀rọ̀ nípa bí àwùjọ oríṣiríṣi ní orílẹ̀-èdè agbáyé ṣe ń dẹ́yẹ sí àwọn lgbtq pẹ̀lú bí àwọn orílẹ̀-èdè... |
akwaeke emezi akwaeke emezi jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó wá láti ẹ̀ya lgbo ó jẹ́ òǹkọ̀wé tamil àti olórin orí ẹ̀rọ fídíò ẹni tí wọ́n mọ̀ dára jùlọ fún ti debut novel freshwater ti ọdún 2018 ìgbésí ayé e rẹ̀ bàbá tí ó bí emezi jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà nígbàtí ìyá rẹ wá láti tamil ní orílẹ̀-èdè indian ìlú aba ní o... |
ìjèbú awọn eniyan ijebu jẹ agbẹ-gbẹ ti o wa lati orilẹ-ede naijiria wọn jẹ apakan ti awọn eniyan yoruba ti o gbooro ti o jẹ abinibi si iha iwọ-oorun iwọ-oorun yoruba ti o wa ni guusu iwọ-oorun orilẹ-ede naa awọn eniyan ijebu sọ ede ijebu ede ti ede yoruba apejuwe ijebu pin awọn aala ni ariwa pẹlu ibadan ni iwọ -oorun p... |
ayoola akinwole professor of aquaculture and water resources management wọ́n bí ọ̀jọ̀gbọ́n ayọ̀ọlá olúṣẹ́gun akínwọlé ní ọjọ́ kẹfà oṣù okúdù ọdún 1969 sí ẹbí akínwọlé ti ìdílé akínàjó ní ìlú ìbàdàn ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ orílẹ̀èdè nàìjíríà ètò ẹ̀kọ́ ati iṣẹ́ rẹ̀ ayọ̀ọlá lọ sí yunifásítì iṣẹ́ àgbẹ̀ ti ìlú abẹ́òkúta - university ... |
matthew blaise matthew nwozaku chukwudi blaise jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó má ń jafitafita lórí àwọn ẹ̀tọ́ nípa queer iṣẹ́ ní oṣù kẹta ọdún 2020 lẹ́hìn tí wọ́n pa ọmọkùnrin gay kan ní ilé nàìjíríà blaise ṣe ìdásílẹ̀ ìpolongo lórí ẹ̀rọ ayélujára tí twitter pẹ̀lú ani kayode somtochukwu àti victor emmanuel àwọn mẹ́tẹ... |
aderonke apata aderonke apata tí a bí ní ogúnjọ́ oṣù kínní ọdún 1967 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ń jà fitafita nípa lgbt àti ẹni tí ó tí n wá ibi ààbò tẹ́lẹ̀ àwọn media káàkiri ni wọ́n mọ aderonke nítorí ọ̀ràn ibí ààbò rẹ ní ilé gèésì united kingdom apata ni olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ aláànú kan tí wọ́n ń pè ní african rain... |
denrele edun adenrele oluwafẹmi ẹdun tí gbogbo ènìyàn mọ sí denrele tí a bí ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹfà ọdún 1981 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó ma ń gbà àlejò lórí tẹlifísànù denrele ni wọ́n ti mọ̀ pẹlú orísirísi àwọn àmì ẹ̀yẹ tí ó ma ń gbà ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àmì ẹ̀yẹ ni olùgbàlejò orí tẹlifísànù yí ti gbà lára wọn ni àmì ẹ̀... |
fẹ́mi adéṣínà fẹ́mi adéṣínà jẹ̀ ọ̀kan lára akọ̀wé ìròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríààti ọ̀gá àgbà agbani nímọ̀ràn lórí ọ̀rọ̀ ìròyìn àti afẹ́fẹ́ lábẹ́ ìjọba ààrẹ muhammadu buhari ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ọ̀gbẹ́ni fẹ́mi adéṣínà lọsí ilé ẹ̀kọ́ gíga fásitì ọbáfẹ́mi awólọ́wọ̀ ti ìpínlẹ̀ ọ̀ṣunbakan naa ó tún lọ sí ilé èkọ́ ìmọ̀ ìṣòwò ní ìl... |
fẹ́mi adéṣínà |
noni salma noni salma tí wọ́n mọ̀ tẹ́lẹ̀ sí habeeb babatunde lawal jẹ́ transgender olùṣe fiimu ònkọ̀wé àti olùfẹ́ fiimu ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó darapọ̀ mọ́ transgender ní orílẹ̀-èdè amẹ́ríkà níbití ọ rìnrìn àjò láti lọ kọ́ ẹ̀kọ́ gba oyè lórí fiimu ṣíṣe ní ilé-ẹ̀kọ́ fiimu tí ó wà ní ìlú new york ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ ... |
àwọn ará zaza àwọn ará zaza dımli — ẹ̀yà ènìyàn ati orile-ede eniyan ni turkey |
elon musk elon reeve musk frs / ˈiːlɒn/ ee-lon ti a bi ni okudu 28 1971 jẹ otaja ati olaju iṣowo oun ni oludasile alakoso ati olukọni oloye ni spacex oludokoowo ipele kutukutu akọsilẹ 2 alakoso ati oluṣapẹrẹ ọja ti tesla inc oludasile ile -iṣẹ alaidun ati alabaṣiṣẹpọ ti neuralink ati openai a centibillionaire musk jẹ ọ... |
pincez tous vos koras frappez les balafons |
david uzochukwu david ejikeme uzochukwu tí a bí ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kejìlá ọdún 1998 jẹ́ olùyàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè austria àti ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà bákannáà ẹni tí ó jẹ́ wípé àwòrán fọ́tòyíyà ni ó dojú kọ jùlọ brussels àti berlin ni uzochukwu ń gbé ó jẹ́ ókan lára àwọn queer ìgbésí ayé àti ìbẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ david ejike... |
tunde oladimeji túndé ọládiméjì jẹ́ onífíìmù-ìfiṣerántí òṣeré olùdarí-eré àti àtọkún orí tẹlifíṣàn ọmọ orílẹ́-èdè nàìjíríà aṣáájú ni nínú àwọn onífíìmù-ìfiṣèrántí ní èdè abínibí ní nàìjíríà òun ní olùdarí aàjírebí ètò òwúrọ̀ tí wọ́n ṣe àfihàn rẹ́ lórí africa magic yorùbá ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ wọ́n bí ọládiméjì ní ìl... |
henry ford henry ford july 30 1863 april 7 1947 jẹ́ ọmọ ilẹ̀ amẹ́ríkà onímọ̀ẹ̀rọ àti oníṣòwò ni óbẹ̀rè iṣẹ́ ṣíṣe ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ ford ní 1896 ó ṣètò bí òṣìṣẹ́ kọ̀ọ̀kan á ṣe máa ṣe páàtì kan lára ọkọ̀ èyí jẹ́ki ṣíṣe ọkọ̀ tuntun jáde lọ́pọ̀ yanturu àti ni ẹ̀dínwó túnbọ̀ rọrùn funọ̀pọ̀ àwọn iléiṣẹ́ ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ àti àwọ... |
supare akoko ilu supare-akoko je ilu ni iwọ oorun guusu ni akoko ijọba agbegbe ni ondo state ni naijira supare fi 100 ibuso ji no si akure olu ilu ise agbe ni ise ile wo |
arigidi akoko ilu arigidi je ilu to wa ni akoko ariwa ìwọ oòrùn ilu ondo state nigeria |
ayetoro ilu ayetoro wa ni latitude 70 12’n ati longitude 30 3’ e ni agbegbe ilu ogun state ayetoro wa ni 35 km ariwa -oorun si ilu abeokuta naijiira olu ilu ogun state ilu naa jẹ ijoko iṣakoso/olu -ilu ti yewa ti a mọ ni deede bi egbado agbegbe ijọba agbegbe ariwa |
al sharpton alfred charles sharpton jr ọjọ́ìbí october 3 1954 jẹ́ alákitiyan ẹ̀tọ́ aráàlú ará amẹ́ríkà ọ̀jíṣẹ́ ìjọ onítẹ̀bọmi atọ́kùn ètò ìbánisọ̀rọ̀ àti olóṣèlú sharpton ni olùdásílẹ̀ àjọ national action network |
india arie india arie simpson ọjọ́ìbí october 3 1975 tó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bíi india arie tàbí indiaarie akọrin àti akọọ̀rọ̀-orin ará amẹ́ríka gbogbo àwọn àwo-orin arie ti tà iye tó ju mílíọ́mù 33 lọ ní amẹ́ríkà àti mílíọ́mù 10 káàkiri àgbáyé ó ti gba she has won four ẹ̀bùn grammy mẹ́rin nínú ìpèníyàn 23 èyí tí àwo-orin r... |
the carpenters the carpenters jẹ́ ẹgbẹ́ were an american olórin pop ará amẹ́ríkà tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ìlú downey ní 1968 pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tó ní richard carpenter àti karen carpenter |
the ghost and the tout the ghost and the tout tí a mọ̀ sì abaraméjì àti ọmọ ìta jẹ́ eré oníse orílẹ̀ èdè nàìjíríà ti ọdún 2018 tí olùkọ̀tàn àti olùdarí rẹ̀ jẹ́ charles uwagbai àwọn ògbóǹtàrìgì òṣèré bíi sambasa nzeribe toyin abraham rachael okonkwo àti omowumi dada ni àwọn tí ó kópa ìṣaájú eré oníṣe náà di àfihàn tó dá... |
love castle 'love castle' jẹ́ eré nàìjíríà tí ó jáde ní ọdún 2021 tí desmond elliott sì ṣe adarí eré náà beatrice fúnkẹ́ ògúnmọ́lá àti victor ògúnmọ́lá ló gbé eré náà jáde eré náà dá lórí iṣẹ̀ṣe àti mọ̀lẹ́bí lára àwọn gbajúmò tí ó kópa nínú eré náà ni rachel oniga zack orji desmond elliot kehinde bankole jide kosoko àt... |
nafisat abdullahi nafisat abdulrahman abdullah tí ó gbajúmò gẹ́gẹ́ bíi nafisat abdullahití a bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kìíní ọdún 1992 jẹ́ òṣèré adarí eré ayàwòrán àti oníṣòwò láti ìlú jos ní ìpínlẹ̀ plateau ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì ẹ̀yẹ lára wọn sì ni afro hollywood award2017 mtn award2016 amma award2015 àti city peop... |
tunbosun aiyedehin tunbosun aiyedehin tí a bí ní ọjọ́ ogún oṣù kẹfà ọdún 1969 tí ó gbajúmò gẹ́gẹ́ bí tuby jẹ́ òṣèré ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó gbajúmọ̀ fún ipa two brides and a baby àti kpians the feast of soul iṣẹ́ ó kópa nínú eré bíi hakkunde troubled waters moth to a flame hell or high water lockdown dear bayo mrs mrs... |
dudley sutton dudley sutton april 6 1933 je osere ara ilẹ̀ọba aṣọ̀kan |
the tourist 2021 film ere onise the tourist je sinima ti orile-ede russia ti andrey batov se adari re ti sergei shcheglov si je onkotan ere naa lare osere lami-laka ti o won kopa ninu re ni sergey pavlov ti osi je olu eda-itan ti aleksey shevchenkov richard sseruwagi marika lindström sten ljunggren ati philip lithner n... |
amotekun |
sikiru adesina |
cathedral church of christ lagos ilé ìjọsìn katidira ti christ marina lagos jẹ́ katidira anglican kan ní lagos island ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà |
odò niger |
a trip to jamaica ìrìn-àjò kan sí ìlú jàmáíkà jẹ́ erẹ́ oníṣe àgbéléwò aláwàdà nàìjíríà ti ọdún 2016 tí robert peters ṣe olùdarí pẹ́lú ayọ̀ mákùn fúnkẹ́ akindélé nse ikpe etim àti dan davies ẹrẹ́ oníṣe àgbéléwò náà sọ ìtàn nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó ṣẹlẹ̀ sáwọn tọkọtaya kan tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣègbéyàwó ní ilé àwọn mọ̀lẹ́bí wọn lẹ... |
tade ogidan akíntádé ògìdán aka tádé ògìdán tí a bí ní osù kejeọdún 1960 jẹ́ òsèré o ǹ kọ̀tàn olùgbéjáde àti olùdarí eré oníse ti ilẹ̀ nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé a bíi sí ìlú èkó ní ilẹ̀ nàìjíríà sínú ẹbí ọ̀gbẹ́ni akinọlá àti rachael ògìdán ó dàgbà ní sùúrùlérè agbègbè ti ìpínlẹ̀ èkó ní ilẹ̀ nàìjíríà ẹ̀kọ́ ó lọ ilé ẹ̀... |
bolot feray bolot feray jẹ eré oníṣe aláwàdà seychellois ti ọdún 1995 tí jean-claude matombe jẹ́ olùdarí marie-therese choppy sì ṣe àgbéjáde rẹ̀ ògbóǹtarìgì òsèré alain belle ni ipa titular tí charles decommarmond jenita furneau antonia gabriel ati marie lista kó ipa àtìlẹyìn o da lori ere kan ati ṣafihan aṣa àti ìṣẹ̀d... |
benedicta gafah a bí benedicta gafah ní ọjọ́ kíní oṣù kẹ̀sán ọdún 1992 ó jẹ́ òṣèré ilẹ̀ ghana tí ó ń ṣàgbéjáde eré oníṣe ó ṣe ìfarahàn nínú àwọn eré oníṣe ti ghallywood àti kumawood tí ó jẹ́ “mirror girl” “azonto ghost” àti “april fool” ó jẹ́ olùfọwọ́sí ilé iṣẹ́ zylofon media inú ire benedicta bẹ̀rẹ̀ sí í fún àwọn aláì... |
adé láoyè adé láoyè jé òsèré eré ìtàgé a bí ní ọjọ́ kàrún oṣù kẹ̀rin ó dàgbà ní apákan ìlú ìbàdàn àti ìlú èkó ó jẹ́ akéèkọ́ artsjáde ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìpínlẹ̀ pennsylvania ó ní àwọn ìwúrí lọ́pọ̀lọpọ̀ nínú eré ìtàgé tv àti eré oníse o ti ṣeré pẹ̀lú àwọn ilé iṣẹ́ ìṣèré olókìkí bíi the walnut street theatre àti the ard... |
mavis adjei mavis adjei jẹ́ oṣ̀eré orílẹ̀ ède ghana kan tí ó ń gbé ní orílẹ̀ ède ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ adjei jẹ́ ọmọ ìlú akwatia ní ilà-oòrùn ẹkùn ti ghana ó lọ ilé ẹ̀kọ́ girama swedru secondary school ní àárín ẹkùn ghana láti ọdún1994 sí ọdún 1996 iṣẹ́ tó yàn láàyò pẹ̀lú àwọn eré oníse tí ó lé ní márùndínlọ́gbọ... |
how to steal a country how to steal a country tiata bi att stjäla ett land jẹ́ eré oníse tí ó jẹ mọ́ itan-akọọlẹ south africa ti ọdún 2019 tí rehad desai ṣe olùdarí òhun pẹ̀lú anita khanna àti zivia desai keiper jọ sàgbéjáde rẹ̀ eré oníse náà rọ̀gbà yí títú aṣírí ìwà ìbàjẹ́ tí wọ́n fi ẹ̀sùn rẹ̀ kan ààrẹ tẹ́lẹ̀rí jacob ... |
place of weeping place of weeping ti tiata bi afrika - land der hoffnung jẹ ere-orí ìtàgé ti orílẹ̀ èdè south africa kan ti ó jáde ní ọdún 1986 darrell roodt ni ó ṣe olùdarí tí anant singh ṣe agbátẹrù fun place of weeping productions àwọn ìràwọ̀ oṣèré james whyle gcina mhlophe àti charles comyn ni ó síwájú ipa eré onís... |
naa ashorkor a bí naa ashorkor ní ọjọ́ kẹrìrínlélóguń oṣù kọkànlá ọdún 1988 orúkọ tí a tún mọ̀ọ́ sí ni nisirine naa ashorkor mensah-doku ó jẹ́ òṣèré ilẹ̀ ghana kan tí ó sì jẹ́ agbóhùn sáfẹ́fẹ́ ní ilé iṣẹ́ asaase radio ile-iṣẹ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ó wà ní accra ó jẹ́ olókìkí ní pa sẹ̀ ipa tí ó kó nínú the perfect picture ... |
agbezin bamidele george a bí ògbẹ́ni agbezin bamidele george ní ojọ kẹtàdínlọgbọn oṣù keje ọdún 1973 ní erékùṣù èkó ní ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀ẹ̀de nàíjíríà sínú ìdílé olóyè agbezin latí ilu togo tó sì fẹ́ ọmọ ìlu nàíjíríà níyàwóolóyè agbezin fúnrarẹ̀ jẹ́ agbẹ́gílére bamidele george fúnrarẹ̀ yan isẹ̀ fífí ọ̀dàdárà bamidel... |
finding hubby finding hubby jẹ èrè fílmù ire ìfẹ tí a ṣe lati ọwọ femi ogunsanwo awon akopa ninu ere na ni kehinde bankole munachi abii ade laoye and omowunmi dada o jẹ aṣamubadọgba iboju ti bulọọgi ti tunde leye kọ idite finding hubby sọ itan ti oyin clegg omidan kan ti o je ọmọ ọdún 35 ati awọn ọrẹ rẹ bi wọn ṣe sa ip... |
abẹ́lé abẹ́lé jẹ́ ìlànà mímú àwọn ẹranko àti ewéko látinu igbó wásílé lati múwọndára tàbí yíwọnpadà fún lílò àwa èníyàn bóyá fún ónjẹiṣẹ́aṣọoògùnbàtà àtibẹ́ẹ̀lọ ohun ọ̀gbìn láti nkan bii ẹgbẹ̀rún ọdún mẹ́wàá sẹ́yìn 10000 years làwọn ènìyàn ti n ṣàwárí àwọn ohun ọ̀gbìn onírúunrú láàárín àwọn àgbègbè bíi tígírísìefurete ... |
the wedding party fíìmù 2016 the wedding party jẹ́ fíìmù àgbéléwò apanilẹ́rìn-ín àti ajẹmọ́fẹ̀ẹ́ ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó jáde lọ́dún-un 2016 tí kemi adetibasì jẹ́ olùdarí fíìmù náà àfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde lọ́jọ́ kẹjọ oṣù kẹsàn-án ọdún 2016 ní toronto international film festival ní canada àti lọ́jọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n o... |
michelle attoh michelle attoh jẹ́ òṣèré orílẹ̀ èdè ghana kan olugbóhùn sáfẹ́fẹ́ lórí amóhùnmáwòrán àti alakoso fún marketing and events company wọ́n bíi sí orílẹ̀ èdè ghana sínú ẹbí ògbóǹtarìgì òṣèré orílẹ̀ èdè ghana rama brew iṣẹ́ michelle ni olóòtú today's woman lórí tv3 díẹ̀ nínú àwọn ipa mìíràn tí ó ti kópa nínú iṣ... |
afia schwarzenegger afia schwarzenegger aka valentina nana agyeiwaa tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá osù kejì ọdún 1982 sí kumasi ghana jẹ́ oluẹda media ni orílẹ̀ èdè ghana òhun ni olóòtú èto 's morning show yewo krom and 's kokooko show òhun ni aláṣẹ schwar tv lórí youtube àti qas purified water olóòtú èto the breakfast show a... |
beverly afaglo a bí beverly afaglo baah ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kaàrún ọdún 1983 ó jẹ́ òṣèré orílẹ̀ èdè ghana àti olóòtú tv ìgbésí ayé beverly wá láti agbègbe volta ní orílẹ̀ èdè ghana ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú eugene kwadwo boadu baah pẹlu ìrújú díẹ̀ wọ́n sì ní àwọn ọmọbìrin méjì iṣẹ́ beverly kọ́ ẹ̀kọ́ gẹ́gẹ́bí onímọ̀ n... |
the smart money woman nigerian series the smart money woman jẹ fíìmù orílẹ̀-èdè nàìjíríà oloṣeṣe ti o da lórí aramada 2016 ti orukọ n je arese ugwu afihan akoko rẹ̀ jàde lórí africanmagic showcase ní oṣù kẹsan ní ọdún 2020 a ṣè àwọn fíìmù náà lati ṣe iṣe iyasọtọ ati mu ohun ti o wa nínú iwe aramada náà wa si oju aye ak... |
badamasi badamasi aworan ti gbogbogbo jẹ́ ìtàn-ayé nípa olori orílẹ̀-èdè nàìjíríà tẹlẹ ibrahim badamasi babangida ibb obi emelonye lo dari rẹ̀ àti irawo bí enyinna nwigwe tí o ko ipa asiwaju gẹ́gẹ́ bí babangida o jẹ́ fíìmù òṣèlú akọkọ nollywood tí o jẹ́ okan gboogi idite badamasi sọ ìtàn babangida láti ipilẹṣẹ rẹ̀ ní a... |
torsten haß torsten haß inagijẹ kim godal ti a bi lori 21 oṣu kọkanla 1970 je olukawe ara orile-ede jẹ́mánì o kọ ẹkọ ni stuttgart ohun na tun lo je oludari fun ile -ikawe ti ile yunifasiti kehl am rhein baden-württemberg lati 1997 de 2014 o ti jẹ olori ile -ikawe ti ile yunifasiti ludwigshafen am rhein rhineland-palati... |
eddie coffie eddie coffie 19592015 jé àgbà òsèré ará ghana ààrẹ ẹgbẹ́ àwọn òsèré orílẹ̀ ède ghana gag àti olùsọ́àgùtàn ó ṣe ìfihàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn erè oníse ilẹ̀ ghana bí bob smith's diabolo dirty tears sinking sands ati a northern affair iṣẹ́ ní ọdún 1992 coffie fara hàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré oníse ti ilẹ̀ gha... |
aderonke adeola adérónkẹ́ adéolá jẹ́ olùdarí eré oníse ti orílẹ̀ èdè nàìjíríà kan òǹkọ̀tàn onísòwò nípa oge síse olùkọ̀tàn àti olùdásílẹ̀ ó gba ẹ̀bùn unesco ní bi ayẹyẹ ní ọdún 2019 fún ìwé ìtàn rẹ́ àwani ó tún jẹ́ òǹkọ̀wé fún ìwé ìròyìn the guardian àti thisday iṣẹ́ adéolá jẹ́ akẹ́ẹ̀kọ́ jáde ti ẹ̀ka ìtàn ó ti ṣiṣẹ́ tẹ... |
erica nlewedim erica ngozi nlewedim tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá osú kẹta ọdún 1994 jẹ́ ọmọ orílẹ̀ ède nàìjíríà àríwòse gbajúgbajà asàfihàn orí amóhùnmáwòran àti alákóso beluxia hair ó jáwé olúborí níbi ìdíje àwọn ọmọbìrin tí ó rẹwà jùlọ ní orílẹ̀ ède nàìjíríà ní ọdún 2014 tí wọ́n sì yán láti jẹ́ ọ̀kan lára akópa nínú gbajúg... |
sneh gupta sneh gupta tí a bí ní ọjọ́ kejìlá osù kàrún ọdún 1957 jẹ́ olùdarí alásẹ sucheta kriplani shiksha niketan sksn ilé-ìwé ibùgbé fún àwọn ọmọ tí ó ní ìpènijà ti ara a mọ̀ọ́ fún iṣẹ́ rẹ̀ lórí èto amóhùnmáwòrán ' àti ' bákańnà pẹ̀lú ipa tí ó kó gẹ́gẹ́ bí ọmọba-bìnrin sushila nínú eré ó tún dá ilé-iṣẹ́ tí ó se ìṣel... |
àtòjọ àwọn aláwàdà ọmọ nàìjíríà |
catherine kamau catherine kamau karanja tí a bí ní ọjọ́ kẹta osù kejì ọdún 1987 jẹ́ òsèré tí ó gba ààmì ẹ̀yẹ tí gbogbo ènìyàn sì mọ́ ọ́ sí celina tàbí kate actress ó di ẹnití àwọn ènìyàn mọ̀ látàrí ipa tí ó kó nínú eré citizen tv mother in-law níbi tí ó ti kópa celina ó tún kópa nínú àwọn eré mìíràn bí sue na jonie 201... |
language family salaye aroko meta ti oje adamo fun awon ode ati agbe |
list of language regulators salaye aroko meta ti oje adamo fun awon ode ati agbe |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.