raw_text stringlengths 2 128k |
|---|
aliko dangote aliko dangote gcon ojoibi 10 april 1957 jẹ́ onísòwò àti ọlọ́rẹ ará nàìjíríà tí ó olùdásílẹ̀ àti alága ilé-isẹ́ dangote group ilé-isẹ́ aloẹ̀rọ gbàǹgbà ní áfríkà gbogbo ohun ìní rẹ̀ ẹ́ tó us81 billion march 2020 ní january 2020 òhun ni ẹni ọlọ́lájùlọ 88k ni agbaye àti ẹni ọlọ́rọ̀ jùlọ ní ilẹ̀ áfríkà ní oṣù ... |
rasaki akanni okoya |
ìbánisọ̀rọ̀ act of conveying intended meanings from one entity or group to another through the use of mutually understood signs and rules ìbánisọ̀rọ̀ láti inú èdè látìnì communicare tí ó túmọ̀ sí ṣíṣalábàápín jẹ́ ìgbésẹ̀ gbígbé is the act of conveying ìtumọ́ ọ̀rọ̀ láti ọ̀dọ̀ ẹnìkan sí ẹlòmíràn fún ìgbọ́ra-ẹni yé yálà n... |
edgar lungu edgar chagwa lungu ojoibi 11 november 1956 je oloselu ati ohun ni aare ile sambia lowolowo lati january 2015 labe aare michael sata lungu lo je alakoso fun idajo ati alakoso fun eto abo leyin iku ojiji aare sata ni october 2014 lungu je gbigba bi enialedinibo fun egbe oselu patriotic front o padanu idibo al... |
abba kyari olóṣèlú abba kyari oon 23 september 1952 17 april 2020 je oloselu ara naijiria to sise bi oga awon osise fun aare ile naijiria lati august 2015 di april 2020 |
agogo agogo jẹ́ ohun èlò tí a ń lò láti ṣòdiwọ̀n iye wákàtí tí wà nínú ọjọ́ kan ṣoṣo and indicate timeagogo jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ tí ọmọnìyàn ṣe àwárí rẹ̀ láyé ó jẹ́ ọ̀kan lára ohun tí a fi ń ṣe ònkà ọjọ́ oṣù àti ọdún nínú ìmọ̀ nipa aago ohun tí wọ́n gbà wípé agogo ni aago tí ó bá dún gbagaun nígbà tí wọ́n... |
nigeria centre for disease control nigeria centre for disease control ncdc gbọ̀ngàn náìjíríà fún ìjánu àrùn jẹ́ olórí àjọ ètò ìlera ìjọba àpapọ̀ tí ó ń bójú tó ètò àjàkálẹ̀ ààrùn ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà àjọ yìí wà lábẹ́ ìṣàkóso ilé-iṣẹ́ ètò ìlera ìjọba àpapọ̀ federal ministry of health nigeria tí olú ilé iṣẹ́ àjọ náà sì... |
richard akinjide oṣùọlálé abímbọ́lá richard akínjídéadájọ́ àgbà ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí a bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù kọkànlá ọdún 1930 tí ó sì kú ní ọjọ́ kọkànle-lógún oṣù kẹrin ọdún 20204 november 1930 - 21 april 2020ó jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè naijiria ó jẹ́ ògbóǹtarìgì agbẹjọ́rò àgbà olóṣèlú takuntakun àti oníṣòwò ńlá ní ... |
ọdún ìgògò ọdún ìgògò jẹ́ ọdún ìbílẹ̀ yorùbá tí ó ma ń wáyé ní ìlú ọ̀wọ̀ ìpínlẹ̀ òndò ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n ma ń ṣe ọdún yí ní gbogbo oṣù kẹsàn án sí oṣù kẹwàá ní ọdọọdún ní ìbu ọlá fún olorì oronsen tí ó jẹ́ olorì ọba rerengejen lásìkò ọdún yí ọba tí ó bá wà lórí ìtẹ́ àti àwọn olóyè láàfin yóòmúra bí àwọn obìnri... |
fela kuti |
children's day |
ọjọ́ àwọn ọmọdé ọjọ́ àwọn ọmọdé je ojo ti a ya soto lodoodun lati se ajoyo eye fun awon omode lagbaye ojo na yato lati orilede si orile-ede ni odun 1925 ojo awon omode kaakiriaye international children's day koko je yiyasile ni ilu geneva nigba ipade agbaye fun itoju omode world conference on child welfare lati igbana ... |
ọmọkùnrin ọmọkùnrin je ako eniyan to je odo won unlo oro yi lati juwe omode tabi odo nigbati ako eniyan ba dagba won unpe ni okunrin |
boy |
arrow of god ìwé eré onítàn arrow of god arrow of god arrow of god heinemann isbn ni wọ́n gbé jáde tí ọdún 1964 ni ó jẹ́ ìwé àpilẹ̀kọ ti gbajú-gbsjà ònkọ̀wé chinua achebe ìwé yí àti things fall apart pẹ̀lú no longer at ease ni wọ́n sọ wípé wọ́n jẹ́ iwé eré oníṣe onítàn tí ìlapa-èrò wọn dọ́gba jùlọ tí ẹ̀kọ́ibùdó ìtàn àt... |
ìbọn common long range firearm ìbọn jẹ́ ohun èlò ogun tí ẹnìkan lè mú tàbí gbé dání lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo wọ́n ṣe ìbọn fún yínyìn pẹ̀lú ọta tàbí àhàyá ó le ṣeé lò dára dára wọ́n ma ń gbé ìbọn dání pẹ̀lú ọwọ́ méjèjì tí wọn yóò sì fi ìdí rẹ̀ ti èjìká kí ó má ba jábọ́ lásìkò tí wọ́n bá ń yìn ín lọ́wọ́ irúfẹ́ ìbọn wọ̀nyí ni a mọ̀ ... |
babájídé olúṣọlá sanwó-olú |
àwọn ẹ̀yà ìgbò àwọn ẹ̀yà ìgbò tí wọ́n tún ń pè níyíbà tàbí heebo tí àpèjẹ́ wọn ń jẹ́ ni wọ́n jẹ́ àkójọ pọ̀ àwọn ènìyàn tí wọ́n ń gbé ní àrin gbùngbùn ìlà oòrun orílẹ̀-èdè nàìjíríà kò sí ẹni tó mọ pàtó ibi tí àwọn ẹ̀yà yí ti wá ṣáájú kí wọ́n tó kóra jọ sí ìletò tí wọ́n wà lóní ilẹ̀ ìgbò pín sí ọ̀nà méjì àkọ́kọ́ èyí tí ó... |
bí ìpínlẹ̀ èkó ṣe ń dojú ìjà kọ covid-19 ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 2020 ni àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 fìdí sọlẹ̀ sí orílẹ̀-èdè nàìjíríà èyí wáyé látipasẹ̀ arákùnrin italy kan tí ó padà sí nàìjíríà pẹ̀lú ọkọ̀ òfurufú ní ọjọ́ kẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 2020 bí àrùn náà ṣe tànkálẹ̀ ní ìpínlẹ̀ èkó ní ọjọ́ kẹtàdínl... |
okezie ikpeazu okezie victor ikpeazu ojoibi 18 osu kewa 1964 ni gomina ipinle abia lowolowo o bo si ori aga ni may 29 2015 o je omo egbe oselu peoples democratic party won tun diboyan si ipo gomina ipinle abia ninu idibo to waye ni march 9th 2019 |
ahmadu umaru fintiri ahmadu umaru fintiri ojoibi october 27 1967 ni gomina ipinle adamawa lowolowo o fi tele je omo ile igbimo asofin ipinle adamawa nibi ti won ti yan gege bi olori ile asofin o di aropo gomina ipinle adamawa fun igba die leyin igba ti gomina murtala nyako je yiyokuro lori ipo na ni july 2014 ko to gbe... |
umaru fintiri |
mayen adetiba mayen adetiba tí a bí ní ọdún 1954 tí ń ṣe ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ òṣèré tí ó wá padà di ògbóǹkarìgì onímọ̀ ẹ̀rọ ìgbésí ayé rẹ̀ a bí adebita ni ọdún 1954 sí orílẹ̀-èdè nàìjíríà iṣẹ́ tó ní ṣe pẹ̀lú ṣíṣàkọ́ọ́lẹ̀ owó ni ó fẹ́ kọ́kọ́ ṣe àmọ́ ó padà nífẹ̀ẹ́ sí iṣẹ́ ìmò ẹ̀rọ ó fẹ́ délé adetiba wọ́n sì bí ọm... |
all progressive congress |
kemi adetiba kemi adetiba jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó sì jẹ́ olùdarí fídíò orin lóríṣiríṣi aṣẹfíìmù àgbéléwò àti olùdarí ètò lórí tẹlifíṣọ́ọ̀nù tí àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ti hàn lórí channel o mtv base soundcity tv bet àti netflix ìgbésí ayé rẹ̀ ọjọ́ kẹjọ oṣù kìíní ọdún 1980 ni a bí kemi ní ìpínlẹ̀ èkó ìyá rẹ̀ ni mayen adet... |
udom gabriel emmanuel udom gabriel emmanuel ojoibi 11 july 1966 ni gomina ipinle akwa ibom ni naijiria o wa lori aga lati 29 may 2015 leyin igbatowe leyin idibo april 2015 labe egbe oloselu people's democratic party won tun tundiboyan sipo gomina ni ojo 29k osu karun odun 2019 |
priscilla ekwere eleje priscilla ekwere eleje jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ tí ó jẹ olùdarí iṣẹ́ tó ní ṣe pẹ̀lú owó tí à ń ná ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní central bank of nigeria cbn òun sì ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ìbuwọ́lù rẹ̀ hàn lórí owó tí à ń ná ní orílẹ̀-èdè náà ìgbésí ayé àti ètò-èkó rẹ̀ eleje jẹ́ ọmọ ìlú afikpo ní ìpínlẹ̀ ebon... |
wizkid musician |
all progressive congress nigeria |
peoples democratic party nigeria |
peoples democratic party |
ayọ̀ bámgbóṣé ayọ̀ríndé bámgbóṣé ojoibi ọjọ́ 27 oṣù kíní ọdún 1932 jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ ẹ̀dá èdè tí ó sì tún jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tí ó gba oyò ọ̀jọ̀gbọ́n àkọ́kọ́ nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá èdè ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó ti ṣiṣẹ́ ribi ribi nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá èdè tí ó sì ti di ìlú mọ̀ọ́ká àti gbajú-gbajà láàrin àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ lá... |
ayọ̀ bangbóṣé |
ayo bamgbose |
sámúẹ́lì peter |
ìdìtẹ̀gbàjọba ní nàìjíríà ọdún 1966 ìdìtẹ̀gbàjọba ní nàìjíríà ọdún 1966 bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù kíní ọdún 1966 nígbà tí àwọn ṣọ́jà tí inú ń bíi chukwuma kaduna nzeogwu àti emmanuel ifeajuna tí wọ́n pa ènìyàn méjìlélógún nínú èyí tí wọ́n pa mínísítà àgbà fún ilẹ̀ nàìjíríà tẹ̀lẹ̀ àwọn olóṣèlú jànkàn jànkàn àwọn ọ̀gá... |
1966 nigerian coup d'état |
abubakar balewa |
ogun abẹ́lé ilẹ̀ nàìjíríà |
regina hall american actress regina lee hall ọjọ́ ìbí december 12 1970 jẹ́ gbajúmọ̀ ọ̀ṣẹ̀rè aláwàdà sinimá àgbéléwò àti tẹlifíṣàn ọmọ orílẹ̀ èdè amẹ́ríkà |
tisha campbell osere akorin ati onijo ara amerika tisha michelle campbell ojoibi october 13 1968 je osere akorin ati onijo ara amerika won bi ni oklahoma city oklahoma o si dagba ni new jersey o bere ere filmu re ni 1986 ninu filmu alawada little shop of horrors o si kopa leyin igbana ninu ere dirama ile-isr telifisan ... |
mo abudu mosunmola abudu tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ mo abudu tí ó sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ ògbóǹtarìgì agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ẹlẹ́yinjú àánú onímọ̀ràn ìṣàkóso àwọn òṣìṣẹ́ àti ẹni tí a mọ̀ mọ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ forbes fi mo abdul hàn gẹ́gẹ́ bíi obìnrin ilẹ̀ adúláwọ̀ tó lọ́lá jù lọ ni ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀... |
angela bassett osere ara amerika angela evelyn bassett ojoibi august 16 1958 je osere ati alakitiyan ara amerika |
tisha campbell-martin |
damon wayans damon kyle wayans sr ojoibi september 4 1960 je alawada osere olukowe ati atokun ara amerika ati ikan ninu awon ẹbí wayans wayans sise bi alawada ati osere ni gbogbo odun awon ewadun 1980 nigba to kopa ninu ere alawada saturday night live ninu ere alawada in living color gangan ni ebun re ti yo jade gege b... |
arsenio hall alawada osere ati atokun eto telifisan ara amerika arsenio hall ojoibi february 12 1956 je alawada osere atokun eto ibanisoro olukowe ati olootu ara amerika o gbajumo nigba to se atokun eto the arsenio hall show eto ale ibanisoro lori telifisan lati 1989 de 1994 ati lati 2013 de 2014 |
debbie allen deborah kaye allen ojoibi january 16 1950 to gbajumo lasan bi debbie allen je osere onijo oluko-ijo akorin-akowe-orin oludari olootu ara amerika ati omo egbe tele president's committee on the arts and humanities won ti pe loruko ni igba ogun fun ebun emmy o gba ni emeta igba emeji fun ebun tony be ni o si ... |
apartheid |
ápártáìdì ápártáìdì geesi segregation lit aparthood ni sistemu ijoba ìṣègbéraga àwọn òyìnbó to da lori iyasotooto eya ti awon oyinbo fi tipatipa fi sejoba ni orile-ede guusu afrika ati south west africa ti a mo si namibia loni lati odun 1948 titi di 1994 apartaidi je ijoba tipatipa to da lori baasskap tabi ìṣègbéraga à... |
ìṣègbéraga àwọn òyìnbó |
akinloye akinyemi former nigerian army major akinloyè akínyẹmí 19542012 tí wọ́n tún mọ̀ sí sergeant carter jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó dé ipò àṣẹ major nínú iṣẹ́ ológun orí-ilẹ̀ ṣáájú kí ó tó fẹ̀yìn tì ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn afẹ̀sùnkan nípa ìdìtẹ̀ gbàjọbatí wọ́n sì fi sẹ́wọ̀n láàrin ọdún 1987 àti 1995 lásìkò t... |
bolaji akinyemi |
michelle pfeiffer michelle marie pfeiffer tí a bí ní oṣù kẹrin ọjọ́ ọ̀kàn-dín-lọ́gbọ̀n ọdún 1958 jẹ́ òṣèré ará ilẹ̀ amẹ́ríkà kan òṣèré tí ó ní ìlọsíwájú tí iṣẹ́ ìbòjú rẹ̀ ti kọjá ogójì ọdún ó di ọ̀kan nínú àwọn òṣèré hollywood tó jẹ́ àkọṣẹ́mọṣẹ́ tó dùn yàtọ̀ jùlọ ní àwọn ọdún 1980 àti 1990 bákan náà ó jẹ́ ọ̀kan nínú àw... |
list of heads of state of haiti |
àtòjọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ hàítì àyọkà yìí ṣe àtòjọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ hàítì láti ìbẹ̀rẹ̀ ìjídìde àwọn ará hàítì ní 1791 òmìniran gangan jẹ́ fífilọ́lẹ̀ ní 1804 between 1806 and 1820 haiti was divided between the northern state renamed kingdom of haiti in 1811 and the southern republic of haiti between 182... |
shafy bello-akinrimisi nigerian film actress and singer shafy bello tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ òṣèrébìnrin àti olórin orin kíkọ ni ó fi kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ níbi tí ó ti farahàn nínú orin seyi sodimu tí love me jeje jẹ́ àkọ́lé rẹ̀ ni ọdún 1997 ìgbésí ayé àti iṣẹ́ tó yàn láàyò ìlú america ni shafy dàgbà sí tí ó s... |
samuel adémúlégún samuel adéṣùjọ adémúlégún jẹ́ ọ̀gá kan lábẹ́ ilé-iṣẹ́ ológun ilẹ̀ nàìjíríà òun ni ọ̀gá àgbà àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ ní ọdún 1966 tí ó dì dé ipò ọ̀gágun pátá pátá fún àwọn ọmọológun ilẹ̀ ní ilẹ̀ nàìjíríà ó gba ipò ọ̀gá 'officer corps níbi iṣẹ́ ológun ní ọdún 21949 òun àti aguiyi ironsi zakariya maimalari àt... |
zakariya maimalari zakariya maimalari jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ ológun ilẹ̀ nàìjíríà tí ó dé ipò brigadier-general tí wọ́n sì ṣekú pa á nínú ìdìtẹ̀gbàjọba ọdún 1966 òun ni adárí pátá pátá fún ikọ̀ ológun 2nd brigade ti ìlú àpápá ní ìpínlẹ̀ èkó ní ọdún 1966 ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí maimalari ní ìpínlẹ̀ yobe ó lọ síilé-ẹ̀kọ... |
ojoma ochai ojoma ochai tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ olùdarí arts ti west africa fún british council ó ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ àdáni àti ti ìjọba ní uk àti west africa láti pèsè àwọn iṣẹ́ lóríṣiríṣi fún ìdàgbàsókè ìgbésí ayé àti ètò-èkó rẹ̀ iṣẹ́ chemistry ni ojoma kọ́kọ́ fẹ́ lọ kà nílé ìwé àmọ́ ó padà ṣe art... |
lateefah dúrósinmí lateefah moyọ̀sọ́rẹ dúrósinmí tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù keje ọdún 1957 jẹ́ olùkọ́ àgbà ti chemistry àti gíwá tó rí sí ọ̀rọ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní obafemi awolowo university tí ó wà ní ilé-ifẹ̀ ìgbésí ayé àti ètò-èkó ọjọ́ keje oṣù keje ọdún 1957 ni a bí dr lateefah sínú ìdílé williams bàbá rẹ̀ ni olóògbé a... |
isoken ogiemwonyi isoken ogiemwonyi tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ olùdarí the obsidian way àti oníṣòwò tó dá zazaii sílẹ̀ ó máa ń rán aṣọ ó sì tún máa ń pèsè àwòrán fún aṣọ rírán lóríṣiríṣi ètò-èkó àti iṣẹ́ tó yàn láàyò university of nottingham ni ogiemwonyi lọ ti ó sì gboyè llb law hons ní law ó sì tún ṣe p... |
humuani alaga humuani amoke alaga 1900 - 29 january 1993ti gbogbo eniyan mọ si mama humuani alaga jẹ ọmọ ilu ibadan ni ipinle nigeria a bi ni ọdun 1900 ni ilu ibadan nigeria humani jẹ olufilọ ati olutaja alainikankan ti o wa sinu iṣowo ọrọ o ko awọn alainitelorun awọn obinrin ni ọdun 1938 lati beere fun iye owo ti o dọ... |
willie obiano willie obiano ojoibi august 8 1955 je oloselu onile-ifowopamosi ati asiseijoba ara naijiria ohun ni gomina ipinle anambra lowolowo lati odun 2014 |
gboyega oyetola adegboyega oyetola ojoibi september 29 1954 je oloselu ara naijiria ati gomina ipinle osun |
isiaka adeleke |
adegboyega oyetola |
dámilọ́lá anwo-ade dámilọ́lá anwo-ade tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ olùṣàkóso sprout digital development limited tí ó ń bá ṣiṣẹ́ pọ̀ òun sì ni olùdásílẹ̀ codeit ètò-ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ rẹ̀ babcock university ni dámilọ́lá lọ tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa information resources management ní ọdún 2003 wọ ọdún 2007 ó tẹ̀ síw... |
omobola johnson ọmọbọla olubusọla johnson bii ni ọjọ kẹjidinlọgbọn oṣu kefa ọdun 1967 je omo orile ede naijiria o je ikan ninu awon oni imo tekinology oun pelu si ni alaga egbe alliance for affordable internet a4ai o je ojise isọrọ tekinology tele ni abe akoso olori orile ede goodluck jonathan eto ekọ re o ka iwe ni il... |
mọsko |
mọ́skò rọ́síà |
little walter marion walter jacobs may 1 1930 february 15 1968 tó gbajúmọ̀ bí i little walter jẹ́ olórin akọrin àti akọ̀wé-orin blues ó jẹ́ ará ilẹl america tí ó kọrin lọ́nà tuntun bí i jimi hendrix ìṣọwọ́korin rẹ̀ mú kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ní ìrètí ohun tí orin blues máa dà lọ́jọ́ iwájú |
marion walter jacobs |
notorious big |
berry gordy berry gordy iii known professionally as berry gordy jr born november 28 1929 je oga ile-ise rekoodu olootu awo-orin akowe-orin olootu filmu ati olootu eto telifisan ara amerika ohun ni oludasile ile-ise rekoodu motown ati awon apa re |
flower |
òdòdó òdòdó ti a mo nigba miran bi ìtànná ewéko ni eyi to ni ibi atunbi ninu awon ogbin olododo awon ogbin ti a mo si magnoliophyta tabi angiosperms ise aaye ododo ni lati kopa ninu atunbi nipa wiwa ona lati mu omiepon wa ba awon eyin |
toke makinwa toke makinwa bii ni ọjọ kẹta oṣu ọkanla ọdun 1984 je omo orile ede naijiria o je agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati onkọwe o kọ iwe on becoming ni odun 2016 ni osu mọkanla o je adari eto ọkọ owurọ ni ori 937 fm ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ wọn bí toke mali wá ní ọjọ́ kẹta oṣù kọkànlá ọdún 1984 sì ìlú èko ni ipinle nàìj... |
àlùbọ́sà àlùbọ́sà jẹ́ irú ohun ọ̀gbìn kan tí orúkọ sáyẹ́nsì rẹ̀ njẹ́ allium cepa ní èdè látìnì àlùbọ́sà jẹ́ ohun ọ̀gbìn tí ó ta lẹ́nu yẹ́ríyẹ́rí gẹ́gẹ́ bí àwọn ẹ̀mẹ̀wà rẹ̀ tókù bíi |
onion |
josephine okwuekeleke tolefe captain josephine okwuekeleke tolefe tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kejì ọdún 1931 jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti òṣìṣẹ́bìnrin àkọ́kọ́ tí a fún láṣẹ láti jẹ́ adarí àti ọ̀gágun kejì nínú ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ ológun ilẹ̀ nàìjíríà ìgbésí ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ọjọ́ karùn-ún oṣù kejì ọdún 1931 ni a... |
kiki mordi kiki mordi ọjọ́-ìbí ọjọ́ kejìlá oṣù kẹjọ ọdún 1991 jẹ́ oníròyìn agbóhùnsáfẹ́fẹ́ òṣèrébìnrin àti oǹkọ̀wé ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà ó gbà ẹ̀bùn agbóhùnsáfẹ́fẹ́ tó tayọ julọ ni apá ìwọ gúúsù ní nigerian broadcasters merit awards ni ọdún 2016 ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí mordi sì ìlú port harcourt rivers ... |
kadaria ahmed kadaria ahmed tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ akọ̀rọ̀yìn oníṣòwò ìgbéròyìnjáde àti olùgbàlejò lórí tẹlifíṣọ́ọ̀nù bbc ní ìlú london ló ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tó yàn láàyò ó sì ti ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ ìtẹ̀wéjáde rédíò tẹlifíṣọ́ọ̀nù àti àwọn àwùjọ ìgbéròyìnjáde lórí ẹ̀rọ ayélujára ìgbésí ayé àti iṣẹ́ tó yàn lá... |
justin fashanu justinus soni justin fashanu 19 february 1961 2 may 1998 je was an english agbaboolu-elese ara ilegeesi to gba boolu larin odun 1978 titi di 1997 ohun ni egbon john fashanu |
john fashanu john fashanu ojoibi 18 september 1962 je omo baba ara naijiria ati omo iya ara guyana to gba boolu-elese ati atokun eto telifisan ara ilegeesi ohun ati justin fashanu je tegbontaburo |
david beckham david robert joseph beckham born 2 may 1975 je is an english former professional agbaboolu-elese ara ilegeesi to ti feyinti |
emmanuel amuneke |
nahzeem olúfẹ́mi mímìkò nahzeem olúfẹ́mi mímìkò tí wọ́n bí ní ọjọ́ kíní oṣù karùn ún ọdún 1960 jẹ́ onímọ̀ nípa ètò ẹ̀kọ́ àti alákòóso àgbà tẹ́lẹ̀ rí ilé-ẹ̀kọ́ yunifásítì adékúnlé ajáṣin tí ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ti ìpínlẹ̀ òndó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ilé-ẹ̀kọ́ àgbà tí àjọ tí united state transparency international standard us... |
dwayne johnson dwayne douglas johnson ojoibi may 2 1972 to tun gbajumo pelu oruko ijaemu re the rock je osere olootu onisowo ajaemu totifeyinti ati agbaboolu-elese ti amerika ara amerika o je ajaemu fun ile-ise world wrestling federation wwf loni bi wwe fun odun mejo ko to di osere awon filmu re ti pawo to to us ni ame... |
margaret ekpo olóyèmargaret ekpo ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínógún oṣù kẹsàn án ọdún 1914 jẹ́ ajàfẹ́tọ́ àwọn obìnrin olùkérò-jọàti olùfilọ́lẹ̀ ìkópa àwọn obìnrin nínú ìṣèlú àkọ́kọ́ orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì ati olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ ajìjà-n-gbara àwọn obìnrin tó gbé àsíá ìṣọ̀kan ẹ̀yà orílẹ̀-èdè nàìjíríà dání ó... |
oluwatoyosi ogunseye olúwatóyọ̀sí ògúnṣẹ̀yẹ tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ akọ̀ròyìn aṣàtúnkọ àti àyẹ̀wò àkọsílẹ̀ àti adarí iṣẹ́ tó rí sí èdè ti west africa ní bbc world service ó jẹ́ aṣàtúnkọ ìwé-ìròyìn the punch newspaper nígbà kan rí ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn mandela washington fellow ìgbésí ayé àti ètò-èk... |
omotunde adebowale omotunde adebowale david tí orúkọ inagi rẹ jẹ lolo 1 je òṣeré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni ìpínlè nàìjíríà òun sì ní atọkun ètò oga madam lórí wazobia fm 941 ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ omotunde lọ sí ilé ẹ̀kọ́ tí ijebu-ode anglican girls secondary school ó kà ìwé imọ òfin ni ilé ẹ̀kọ́ gíga tí lago... |
didi akinyelure didi akinyelure jẹ́ akọ̀ròyìn orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti britain tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ lóríṣiríṣi university of nottingham ní ó ti kẹ́kọ̀ọ́ jáde lórí chemical engineering ní oṣù keje ọdún 2016 ó gba àmì-ẹ̀yẹ bbc world news komla dumor ní ọdún 2016 bákan náà ó gba àmì-ẹ̀yẹ special excellence alumni laureate ... |
dénrelé adémikìtán ọbasá denrelé adémikìtàn ọbasá 1878-1948 jẹ́ ọmọ bíbí ilé-ifẹ̀ àmọ́ tí ó fi ìlú èkó ṣe ibùgbé ó jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn akéwì ilẹ̀ yorùbá lásìkò ọdún 1920s òun ni olóòtú àgba fún ìwé -ìròyìn ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tí ó ń gbé jáde pẹ̀lú èdè orísi méjì tí ìwé-ìròyìn náà sì jẹ́ ẹkejì irú rẹ̀ tí yóò ma sọ̀ròyìn... |
chika oduah chikaodinaka sandra oduah tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹta ọdún 1986 jẹ́ akọ̀ròyìn ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti ìlú america tí ó sì jẹ́ olóòtú ìròyìn lórí afẹ́fẹ́ akọ̀wé ayàwòrán ó gba àmì-ẹ̀yẹ cnn multichoice african journalists award ní ọdún 2016 látàrí ipa tó kó lórí ìròyìn àwọn ọmọ chibok tí boko haram gb... |
yéwándé akinọlá yéwándé akinọlá tí a bí ní ọdún 1984 jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ àgbà tó ń ṣiṣẹ́ lórí ìpèsè omi ó ń ṣiṣẹ́ fún laing o'rourke gẹ́gẹ́ bíi pricincipal engineer ó sì máa ń ṣolóòtú ètò orí afẹ́fẹ́ kan lórí ìmọ̀ ẹ̀rọ ní channel 4 àti national geographic ètò-èkó rẹ̀ ọdún 1984 ni a bí akinọlá sórílẹ̀-èdè nàìjíríà ó máa ń y... |
ire aderinokun ire adérìnókùn tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ front end developer àti google developer expert òun ni obìnrin àkọ́kọ́ nílẹ̀ nàìjíríà tí ó jẹ́ google developer expert ìgbésí ayé àti ètò-èkó rẹ̀ ire wá láti ìpínlẹ̀ ògùn lórílẹ̀-èdè nàìjíríà a bí sínú ìdílé tayo àti mrs olunfunlola aderinokun lẹ́yì... |
sugar ray robinson sugar ray robinson orúkọ àbísọ walker smith jr may 3 1921 april 12 1989 jẹ́ oníṣẹ́ ìjàẹ̀sẹ́ ará amẹ́ríkà to jìjàdù láti ọdún 1940 di 1965 idú tí robinson ta nínú àwọn ẹ̀ka welterweight àti middleweight mú kí àwọn oniròyìn eréìdárayá ó dá ìtòsípò tó ún jẹ́ pound for pound ẹ̀sẹ́ sí ẹ̀sẹ́ níbi tí wọ́n t... |
funke egbemode funke egbemode tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè nàìjíríà jẹ́ akọ̀ròyìn olùdarí àti aṣàtúnkọ àgbà fún daily telegraph publishing ltd òun sì ni ààrẹ àná fúnnigerian guild of editors ìgbésí ayé àti ètò-èkó rẹ̀ ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun ni a bí funke sí ó bẹ̀rẹ̀ ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní baptist practising primary school ní iwo ní ìp... |
dick tiger dick tiger orúkọ àbísọ richard ihetu august 14 1929 december 14 1971 jẹ́ ajẹ̀sẹ́ tó gba world middleweight àti world light heavyweight championships tiger kó lọ sí liverpool ní ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì láti lọ ṣiṣẹ́ ìjẹ̀sẹ́ àt'ibẹ̀ ló ti kó lọ sí amẹ́ríkà wọ́n fi orúkọ tiger sínú ilé olókìkí ìjẹ̀sẹ́ àgbáyé ní 1991 ìwé-ìr... |
ígbò |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.