raw_text
stringlengths
2
128k
lagos state judiciary
october rain october rain jẹ́ ayẹyẹ tó ma ń wáyé lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo lọ́dún ó jẹ́ àkójọpọ̀ ẹgbẹ́ àwọn oníṣẹ́ ọnà ilẹ̀ nàjíríà ìyẹn 'society of nigerian artits' san àsìkò ayẹyẹ àjọ̀dún yìí ni ọ̀pọ̀ nínú àwọn oníṣẹ́ ọnà náà ma ń ṣàfihàn iṣẹ́ ọnà àtinúdá wọn fáráyé rí àti láti lè ṣègbélárugẹ fún àwọn ènìyàn tí ó ti tiraka láti ...
julie benz julie marie benz ojo ibi ojo kini osu karun 1972 osere birin ile amerika ti a mo si darla ninu buffy the vampire slayer ati angel 19972004 ati rita bennett ninu dexter 20062010 ninu eyi ti o ti gba ami eye satelaiti fun osere birin ti oni ifowosopo ni odun 2006 ati ami eye satun ni 2009 o ko pa ninu roswell ...
hermes rodrigues da fonseca
new money owó tuntun 2018 film new money owó tuntun jẹ́ eré ìtàgé apanilẹrìín tí a gbé jáde ní ọdún 2018 ni orile-ede nàìjíríà tọpẹ ọṣhin ni oludari ere náà nígbàtí ilé isẹ́ inkblot productions àti filmone gbé e jade fíìmù na só ìtàn ọmọbìnrin kan ti o n ba ni ta'jà ti o ni èròngbà láti di aránṣọ ti o wá ṣàdédé rí ìpín...
àpàlà àpàlà jẹ ẹ̀yà orin tí a múwá láti ọ̀dọ̀ àwọn yorùbá ní nàìjíríà ó jẹ́ èyí tí ó gùn lé sítáì pakọ́sàn tí ó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀ ní òpin ọdún 1930 lọ sókè ní ìgbà tí wọ́n ń lò ó láti jí àwọn olùsìn lẹ́yìn ààwẹ̀ lásìkò oṣù mímọ́ lámúláánà ti àwọn ìmọ̀le ìmìtìtì àpàlà gbòòrò si pẹ̀lú àsìkò ó fi orin kúbànì ṣe àtẹ̀gùn tí ó...
ògún festival ọdún ògún jẹ́ ayẹyẹ ọdọọdún tí áwọn ènìyàn yorùbá ìpínlẹ̀ oǹdó nàìjíríà máa ń ṣe fún bíbu iyì fún ògún jagunjagun àti irúnmọlẹ̀ oníṣẹ́ irin tí àwọn yorùbá gbà pé òun ni òrìṣà tí ó kọ́kọ́ dé ilé ayé ìtàn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi ìgbàgbọ́ àwọn yorùbá ògún jẹ́ ọba ó sì jẹ́ bàbá ọ̀rànmíyàn òun sì tún ni ènìyàn àkọ́kọ́ ...
yewande adekoya yéwándé adékọ̀yà bí ni ogúnjọ́ oṣù ṣéẹ́rẹ́ 1983 jẹ́ òṣèré olùdarí àti olótùú eré ọmọ orílẹ̀èdè nàìjíríà ibẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé-ayé àti ẹ̀kọ́ ìlú èkó ni wọ́n bí yéwándé sí ṣùgbọ́n ọmọ ọ̀sọsà-ìjẹ̀bú ni ìpínlẹ̀ ògùn iwọ̀-oòrùn nàìjíríà ó lọ sí ilé - ẹ̀kọ́ bright star nursery and primary kí ó tó tẹ̀síwájú fún ẹ...
tope alabi tọ́pẹ́ àlàbí tí wọ́n tún mọ̀ sí oore tí ò common àti agbo jésù ni a bí i ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1970 ó jẹ́ òṣèré akọrin eré sinimá àti òǹkọrin ìgbàgbọ́ ìgbé ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí tọ́pẹ́ àlàbí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1970 ní ìpínlẹ̀ èkó nàìjíríà fún pa joseph akínyẹlé ọbáyọmí à...
opon ifá ọpọ́n ifá tí wọ́n ń pè ní la mesa de ifá ní látìnnì amẹ́ríkà jẹ́ àtẹ ìṣàyẹ̀wò nínú ìsẹ̀ṣe adúláwọ̀ àti ẹ̀sìn àwọn ẹ̀yà adúláwọ̀-amẹ́ríkà pàápàá jùlọ nínú ifá àti ìsẹ̀ṣe yorùbá babaláwo oníyẹ̀míwò ṣàmúlò ọpọ́n ifá láti lè bá àwọn irúnmọlẹ̀ sọ̀rọ̀ tí wọ́n ó ṣàfihàn èrédìí àti ojútùú sí àdáni àti ìsòro àpapọ̀ àti...
àṣà ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ yorùbá àṣà ìsọmọlórúkọ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn àṣà ilẹ̀ yorùbá orúkọ ṣe pàtàkì gan-an ó sì ṣe kókó gbogbo ohun tí ọlọ́run dá pátá ló ní orúkọ tí wọ́n ń jẹ́ kí a ba lè dá ẹnikọ̀ọ̀kan mọ̀ ni a ṣe máa ń fún wọn lórúkọ yorùbá gbàgbọ́ pé orúkọ á máa fi bí ọmọ ṣe jẹ́ hàn orúkọ á sì máa ro ọmọ àti pé orúkọ ...
anastasios george leventis anastasios george leventis gíríkì december 1902 october 25 1978 jẹ́ ọmọ ilẹ̀ gíríkì tí ó jẹ́ olùṣòwò tí ó dá onírúurú ilé iṣẹ́ kalẹ̀ jáàkiri àgbáyé pàá pàá jùlọ ilẹ̀ adúláwọ̀ tí ó fi kan orílẹ̀ èdè nàìjíríà ìyẹn leventis nigeria plc tí ọba aláké ti ilẹ̀ ẹ̀gbá oba ladapo ademola sì fi jẹ oyè b...
prudence ngozi onyejiaka prudence ngozi onyejiaka jẹ́ sọ̀rọ̀ sọ̀rọ̀ orí asọ̀rọ̀-mágbèsì ní ilẹ̀ nàìjíríà
tèmitọ́pẹ́ adéyẹmí tèmítọ́pẹ́ adéyẹmí jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà tí ó jẹ́ sọ̀rọ̀ sọ̀rọ̀ orí ẹ̀rọ alátagbà
ọmọlọlá ọnà-àdìgún 'ọmọlọlá ọnà-àdìgún jẹ́ sọ̀rọ̀ sọ̀rọ̀ orí ẹ̀rọ asọ̀rọ̀-mágbèsì àti ẹ̀rọ ayélujára ọmó orílẹ̀ èdè nàìjíríà
isimeme ejodame-whyte isimeme ejodame-whyte jẹ́ olùkọ́ tí ó ma ń kọ́ àwọn ọmọdé tàbí ọ̀dọ́ pàápáà jùlọ àwọn ọmó obìnrìn tàbí wúndíá lórí bí wọ́n ṣe lè gbé ìgbé ayé ìrọ̀rùn gẹ́gẹ́gẹ́ bí ohun èlò oàtàkì àwùjọ
lilly aninyei lilly aninyei jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà àti olùdásilẹ̀ 'greenroom nigeria'
seacom
sea me we 5
cma cgm cma cgm ni ile-iṣẹ ọkọ ayọkẹlẹ kan lati faranse o jẹ ọkọ ayọkẹlẹ giga ti kariaye ti transporter
spar spar jẹ alagbata ti ilu okeere ti n ta awọn ọja abuda gẹgẹbi ounjẹ awọn onigbọwọ ati awọn tiketi lotiri
opele ọ̀pẹ̀lẹ̀ pípè rẹ̀ opuele tàbí ocuele ní látìnì-amẹ́ríkà ni okùn ìṣàyẹ̀wò tí wọ́n ń lò nínú ẹ̀sìn ìbílẹ̀ adúláwọ̀ àti àwọn akátá-amẹ́ríkà pàápàá jùlọ nínú ifá àti ìsẹ̀ṣe yorùbá babaláwo oníyẹ̀míwò máa ń lo ọ̀pẹ̀lẹ̀ láti lè sọ̀rọ̀ pọ̀ pẹ̀lú òòṣà ọgbọ́n/ìmọ̀ ọ̀rúnmìlà nínú ìsẹ̀ṣe yorùbá ẹni tí ó lè ṣe àfihàn okùnfà ...
aṣọ òfì aṣọ òfì tàbí aṣọ òkè jẹ́ aṣọ olówùú tí a fọwọ́ hun láti ọwọ́ ẹ̀yà yorùbá ti ìwọ̀ oòrùn nàìjíríà aṣọ òkè túmọ̀ sí aṣọ ìléké ní èdè gẹ̀ẹ́sì ọkùnrin ni ó sáábà máa ń hun-ún wọn a máa fi ṣe ẹ̀wù tí à ń pè nì agbádá ìró obìrin tí à ń pè ní ìró àti àkẹtẹ̀ ọkùnrin tí à ń pè ní fìlà láti inú àṣà ìpínlẹ̀ òǹdóìpínlẹ̀ ògù...
ufm ufm jẹ iṣowo iṣowo ti awọn orilẹ-ede mediterranean ni ibi ti aladani arab ati european union jẹ ẹya egbe ti agbedemeji agbedemeji ufm jẹ ile-iṣowo iṣowo ti o ni iṣowo ni awọn orilẹ-ede united nations
yoruba name orúkọ yorùbá jẹ́ ohun pàtàkì tí àwọn yorùbá ń lò jákè-jádò gbogbo ibi tí wọ́n ti ń sọ èdè yorùbá bí ìbínítógò àti nàìjíríà nípaṣe ìṣe àwọn baba ńlá baba àwọ́n yorùbá eọ́n ń fún ọmọ wọn lórúkọ níbi ayẹyẹ tí ó máa ń wáyé ní ọjọ́ kẹẹ̀jọ lẹ́yìn ìbímọàwọn orúkọ àwọn ọmọ jẹ́ àṣà àtọwọ́dọ́wọ́ nípa ifá dídá tí ọ̀pọ...
dodo ikire dòdò ìkirè jẹ́ oúnjẹ ìbílẹ̀ láti ìlú ìkirè ní gúúsù-ìlà oòrùn ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun ilẹ̀ nàìjíríà láti ilẹ̀ àjẹkù ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà ni wọ́n máa ń lò ṣùgbọ́n ní òní àwọn ènìyàn ti ń lo èròjà ọ̀tun fi ṣe é tíí ṣe ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà tí ó ti pọ́n torí-tìdí ata epo àti iyọ̀ dòdò ìkirè dúdú ó sì tún yí roboto tàbí onígun òkò...
abiku àbíkú àbíkú jẹ́ orúkọ yorùbá tí ó lè túmọ̀ sí 'ẹni tí wọ́n ń bí tí ó ń kú lọ́pọ̀ ìgbà' ìtumọ̀ àbíkú ń tọ́ka sí ẹ̀mí ẹni tókú yálà ọmọdé tàbí ẹni tí ó kú kí ó tó dàgbà ọmọ tí ó kú kí ó tó di pé ó pé ọmọ ọdún méjìlá ni a lè pè ní àbíkú ọmọdé bẹ́ẹ̀ kẹ̀ẹni tí ó kú nígbà tí ó dàgbà tí àwọn òbí rẹ̀ kò ní agbára láti bí...
òrò àyálò yorùbá ọ̀rọ̀-àyálò jẹ́ ọ̀rọ̀ kan pàtàkì tí a yá wọnú èdè yorùbá láti inú èdè mìíràn ó le jẹ̀ láti inú gẹ̀ẹ́ṣì lárúbáwá haúsá àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ kí ó lè bá ohun tí wón fẹ́ mu nínú èdè won àkíyèsí sí wà pé kò sí èdè tàbí àwùjọ kan tí kì í ya ọ̀rọ̀ láti inú èdè kan bí gẹ̀ẹ́ṣì ṣe yá ọ̀rọ̀ bẹẹ náà ni àwùjọ yorùbá ...
àlọ́ àlọ́ ni ẹ̀yà lítíréṣọ̀ alohùn yorùbá tí wọ́n fi ń kọ́ àwọn ọmọdé lẹ́kọ̀ó tàbí dá wọ́n lára yá ó jẹ́ àṣà ìkọ́mọ̀lẹ́kọ̀ó àti ìdárayá fún àwọn ọmọdé àlọ́ lè wáyé nípa sísọ ìtàn kúkúrú akọ́nilọ́gbọ́n tàbí kí ó jẹ́ ìbéèrè àdìtú àkókò ìpàlọ́ alẹ́ pàápàá jùlọ nígbà tí òṣùpá bá tàn ni àwọn àgbà àdúgbò máa ń kó àwọn ọmọdé ...
tọpó àgbádárìgì ìlú tọpó jẹ́ ìlú kán tí ó wà ní eré-kùṣù agbègbè ìlú àgbádárìgì ní ìpínlẹ̀ èkó bákan náà ni ìlú tọpó jẹ́ ibi tí àwọn ajíyìn rere kátólíìkì kọ́kọ́ gbin àgbọn sí ní ilẹ̀ nàìjíríà ní ọdún 1845 ibẹ̀ náà sì ni wọ́n kọ́kọ́ dá ilé ẹ̀kọ́ àwọn olùkọ́ sí ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà
fìlà aṣo òfì fìlà aṣọ òfì aṣo-òkèẹ̀yà fìlà tòmí rìrọ̀ jẹ́ fìlà yorùbá tí wọ́n ń fi aṣo òfì húnhun ṣeòwú àrán tàbí dàmáàsìnínú èdè yorùbá irú rẹ̀ ni wòn ń pè ní fìlàbí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé ọorírun fìlà ni nàìjíríàọ̀pọ̀lọpọ̀ ọkùnrin ni wọ́n ń wọ̀ ọ́ nínú ìran aláwọ̀ dúdú ìmọ́lára òkè fìlà gígẹ̀ sí ẹ̀gbẹ́ kan niìyókù á sì ta...
aso oke hat
ile-iṣẹ amẹrika ti brasil ile-iṣẹ amẹrika ti brasil ni orisun ti o jẹ pataki ti ilana isakoso faili siga ni ilu brasil o ṣẹda ni ojo 2 oṣu kinni ọdun 1838 ati pe o ni ori ile-iṣẹ rẹ ni rio de janeiro gẹgẹbi ofin ti ile-itọju ofin 8159 ti oṣu keje 8 1991 o ni ojuse lati ṣeto tọju tọju fun wiwọle ati ki o ṣalaye ohun-ini...
sọjí cole sọjí cole tí àpèjẹ́ rẹ̀ ń jé olúsọjí henry cole jẹ́ ònkọ̀wé òṣèré adarí eré ìtàgé àti sinimá ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríàwọ́n bí olúsọjí henry cole ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù ọ̀pẹ ọdún 1976 ní òpópónà kókà ní ìlú mushin ní ìpínlẹ̀ èkó ọ̀mọ̀wé cole gba ẹ̀bun nigeria prize for literature ti ọdún 2018 ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ sọj...
olúsọjí henry cole
jesse king jesse king tí gbogbo ayé mọ̀ sí bùgá jẹ́ olórin ilẹ̀ adúláwọ̀ tí ìwọ́hùn orin rẹ̀ jẹ́ ti èdè yorùbà tí gbogbo orin rẹ̀ sìjẹ́ èyí tí ó ǹ gbé àṣà àti èdè yorùbà lárugẹ ní ọdún 2016 ó pè fún ìkún -lápá àwọn ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà láti dìbò gbé ààrẹmuhammadu buhari wọlé kí ààrẹ náà lè mù ètò ọrọ̀ ajé ilẹ̀ nàìjíríà dú...
national youth service corps àjọ eletò agùnbánirọ̀ ilẹ̀ nàìjíríà tí a mọ̀ sí nysc the national youth service corps jẹ́ ètò tí ìjọba ilẹ̀ nàìjíríà gbé kàlẹ̀ fún àwọn ọ̀dọ́ langba tí wọ́n ti kẹ́kọ̀ọ́ jáde ilé ẹ̀kọ́ ńlá ńlá jáàkiri ilẹ̀ nàìjíríà léte àti lè jẹ́ kí àwọn ọ̀dọ́ wọ̀yí ó lè mú iṣẹ́ ìdàgbà sókè ilẹ̀ baba wọn ní...
eba ẹ̀bà jẹ́ óúnjẹ ní ilẹ̀ yorùbá àti àwọn ẹ̀yà míràn tó yí wọn káẹ̀bà nínú àwọn ẹ̀yà óúnjẹ tí a mọ̀ sí òkèlè ní èdè yorùbá swallow ní èdè gẹ̀ẹ́sì àwọn yorùbá àti àwọn ẹ̀yà míràn tó yí wọn ká fẹ́ràn ẹ̀bà pàápàá jùlọ àwọn àgbàlagbà nítorí wípé ó ma ń tètè yóni kìí sì í tètè dà nínú ẹniẹ̀bà kìí ṣe óúnjẹ tí ń gbani lákòók...
steven spielberg <ns>0</ns> <revision> <parentid>530356</parentid> <timestamp>2020-03-12t061033z</timestamp> <contributor> <username>oluwapelumi2020</username> </contributor> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> steven allan spielberg kbe omri ti a bí ni ọjọ́ kejìlá 18 1946 jẹ olùdarí améríkà kan olùdás...
sharon stone sharon vonne stone ti a bi ni oṣu kẹwa 10 1958 jẹ oṣere amerika oludasiṣẹ ati awoṣe apẹrẹ lẹhin ti o ṣe atunṣe ni awọn iṣowo tẹlifisiọnu ati awọn ipolowo apẹrẹ o ṣe ayẹyẹ fiimu rẹ gẹgẹbi afikun ni oju -iwe ere-iwe stadust memories 1980 ti woody allen ni akọkọ ọdun 1980 ọgbẹni wes craven jẹ ibukún iroyin 19...
tunde adeniran túndé adéníra jẹ́ olùkọ́ ilu naijiria olóṣèlú diplomat àti alákòóso ilé-ẹ̀kọ́ gíga oṣiṣẹ igbimọ ti àjọ ìṣọ̀kan àgbáyé ṣááju kí ó tó dara pọ̀ mọ́ ìṣèlú ní ọdún 1998 ni ó ti kọ́kọ́ fẹyìn tì bí olùkọ́ni nípa ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ìṣèlú ní ilé-ẹ̀kọ́ yunifásítì ìlú ìbàdàn o jẹ onkọwe ti awọn nọmba ati awọn iwe ohun ak...
ayo awọn igbasilẹ ayo tun jẹ iyatọ ti o wọpọ ti ọrọ naa yo ayo ayọ ayọ ati ayo le tọka si awọn eniyan woôn / ɑː j oʊ / ni a wọpọ yorùbá fi orukọ o le wa fun a abo ati ki o kan akọ ayọ ni yoruba tumọ si iyọ
oluwole oke oluwole busayoô oke bi 28 april 1967 je omo naijiria onisowo okowo ati oloselu ti o ti wa sìn ni ile awọn aṣoju oun ni igbimọ alaga lori ijoba ọlọhun ni awọn aṣoju ile asofin ti orile-ede naijiria ti o wa ni agbegbe ipinle obokun / oriade ti ipinle osun labẹ ijọba people's democratic party nigeria eko oke l...
lanre tejuosho ọmọọba olanrewaju adeyemi tejuoso tí a bí ní ọdún 1964 jẹ́ olóṣèlú naijiria kan ó ń ṣiṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ gẹ́gẹ́ bí i òṣìṣẹ́ ìgbìmọ̀ láti ìpínlẹ̀ ògùn ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí lanre tejuoso sí ìlú abẹ́òkúta sí ìdílé ọba ti hrm oba dr adedapo tejuoso con karunwi iii oranmiyan osile ti òkè-ọ̀nà ẹ̀gbá àti...
tejuosho tejuosho tabi tejuoso le tọkasi lati
tejuosho market tejuosho market jẹ ile-iṣowo ti o wa ni ilu ojuelegba -itire ni yaba igberiko kan ni ipinle eko ni gusu-iwọ-oorun naijiria oja ti o pin si awọn ọna meji igbese kini ati ipele keji ni awọn ibi-itaja ti o ni titiipa ni 223 awọn ile-itaja ni ile -itaja mẹrin ati ile-itaja ati awọn ile-iṣẹ ifowopamọ awọn il...
adédàpọ̀ adéwálé tẹ́júoṣó ọba adédàpọ̀ adéwálé tẹ́júoṣó ni osilẹ̀ ti òkè ọnà ni ilẹ̀ ẹ̀gbá òun ni bàbá tí ó bí sẹnetọ lánre tẹ́júoṣó wọ́n bí ọba adédàpọ̀ adèwálé sínú ẹbí joseph ṣómóyè tẹ́júoṣó nígbà tí orúkọ ìyá rẹ̀ ń jẹ́ esther bísóyè tẹ́júoṣó ẹni tí ó jẹ́ ọmọọmọ fún ọba kárunwí kínní ti òkè ọnà
adewale oke adekola adéwálé oke adékọ́lá fistructe fice con 26 oṣu kẹta 1932 - oṣu karun 1999 jẹ́ onímọ̀ ero omowe òǹkọ̀wé ati alabojuto ó jẹ́ ọ̀gá àgbà fún èka ìmọ̀ ẹ̀ro ̣ni ilé kíkó àti àtúnṣe ọ̀nà ilé-ẹ̀kọ́ yunifasiti ti èkó òun ni ìgbà kejì alákòóso ìgbìmọ̀ ti ilé-ẹ̀kọ́ gíga yunifásítì abubakar tafawa balewa báka...
wole soyinka prize for literature in africa wolé sóyínká ébùn fún lítíréṣọ̀ ní afíríkà jẹ́ àmì-kíkọ kíkọ pan-afirika ti wọ́n funni ni ọdún méjì si iṣẹ ti o dara julọ ti afirika gbejade o ni iṣeto nipasẹ lumina foundation ni ọdun 2005 ni ibowo fun iwe-aṣẹ nobel ti akọkọ ni ile afirika ni iwe-iwe wole soyinka o funni ni ...
abraham alechenwu abrahim alechenwu albanian abraham aleçenu ti a bi ni 26 oṣù 1986 jẹ awọn agbẹbọọlẹ-ije naijiria kan ati aṣoju afẹsẹgba kan o lo ọpọlọpọ ninu iṣẹ rẹ ni albania nibiti o ti ṣe atẹyẹ daradara pẹlu elbasani ati tirana ati pe a ṣe apejuwe rẹ ni ẹẹhin ti o dara julọ ni albanian superliga
abdulla baba fatadi abdulla baba fatadi tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejì oṣù kọkànlá ọdún 1985 2nd november 1985 jẹ ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè nàìjíríà agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá fún orílẹ̀ èdè bahraini ó jẹ́ olùdarí fún ẹgbẹ́ al jahra orukọ àbísọ rẹ̀ ni babatunde fatai ó gbá bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá fún orílẹ̀ èdè naijirialábala àwọn ọ̀jẹ̀wẹ́wẹ́...
adebayo gbadebo adébáyọ̀ gbádébọ̀ tí abí ní ọgbọ̀njọ́ oṣù karùn-ún ọdún 197430 may 1974 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ẹlẹ́sẹ̀ àti ọ̀jan lára àwọn akọ́ni mọ̀ọ́gbá ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ìgbésí ayé rẹ́ adébáyọ̀ gbádébọ̀ n gbé oẹ̀lú ìyàwó àti àwọn ọmọ rẹ̀ mẹ́ta
yinka ayefele olayinka joel ayefele mon jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti akọrin ìhìnrere ní ìlànà kìrìsìtẹ́nì ó sì tún jẹ́ olóòtú ètò orí rédíò àti olùdásílẹ̀ fresh àti blast fm tó wà káàkiri apá ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀pẹlpẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí ayefele ipoti-ekiti èyí tó jẹ́ ìlú kan ní ìpínlẹ̀ èkìtì tó wà ní apá ì...
alexander akínyẹlé alexander babátúndé akínyẹlé cbe ni wọ́n bí ní 5 september 1875 - 1 october 1968 je bíṣọ́ọ̀bù àgbà àkọ́kọ́ ní ìjọanglican diocesan ní ìlú ìbadàn ní orílẹ̀ èdè nàìjíríà igeria òun ni èni àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ìbàdàn tí ó kọ́kọ́ gba oyè ba ní ilé ẹ̀kọ́ fásitì tí ó sì kọ́kọ́ jẹ́ olùdásílẹ̀ ilé ì...
lánre towry-coker dr lanre towry-coker friba ni wọ́n bí ní ọdún 1944 tí ó sì jẹ oníṣẹ́ ayàwòrán ilé olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ nàìjíríà ó ti ṣiṣẹ́ lábẹ́ ìjọba àti aládàáni rí tí ó sì jẹ́ kọmíṣánà àkọ́kọ́ fún iṣẹ́ àti ilégbèé ní ìpínlẹ̀ èkó nígbà kan rí ìgbésí ayé àti isẹ́ rẹ̀ti bàbá láre jẹ́ onímọ̀ civil engineer ọmọ oríẹ̀ èdè n...
oluwafemi olaiya balogun olufemi olaiya balogun a bi ni ojo kandilogun oṣu kẹwa 1953 je oludari agba tile tile federal university of agriculture abeokuta nijiriya
olusola bandele oyewole olusola bandele oyewole abini oṣu kẹsan ogbon ọjọ 1955 ni ipinle kaduna nigeria jẹ olukọni ti nigeria ti imọ imọ-ẹrọ ati imọ-ẹrọ olutọju ẹkọ ati oludari alakoso giga ti university of agriculture abeokuta
ade akinbiyi adeola oluwatoyin akinbiyi ti a bi ni ijo kewa oṣu kẹwa ni odun 1974 jẹ ẹlẹsẹ ẹlẹsẹ ẹlẹsẹ mẹẹdogun kan ti naijiria ti o ṣiṣẹ ni iwaju
gẹ̀lẹ̀dẹ́ gẹ̀lẹ̀dẹ́ jẹ́ òrìṣà kan nílẹ̀ yorùbá tó níṣe pẹ̀lú àwọn obìnrin tí ó sì ń ṣàfihàn ipa àwọn obìnrin ní ilẹ̀ yorùbá pàápàá àwọn akínkanjú àti àwọn orìṣà tó ní ṣe pẹ̀lú àwọn obìnrin pẹ̀lú agbára tó rọ̀ mọ́ ẹ̀mí àìrí bí ẹ̀mí àjẹ́ tí wọ́n ní ẹ̀wẹ̀ àwọn agbára wọ̀nyí ní ìpalára fún àwùjọ ìdí nìyí tí wọ́n fi ń lo òr...
ìlù sákárà ìlù sákárà jẹ́ ìlù kan lára àwọn ìlù mẹ́rin tó jẹ́ ẹbí kan náà nínú ìlù tó ṣe gbòógì mẹ́rin nílẹ̀ yorùbá àwọn èyà ìlù tó kù ni dùndún tàbí gángan bàtá àti ìlù gbẹ̀du ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ìlù òkè yí ni wọ́n jẹ́ ìwọ̀n ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ sì ìyá ìlù tó ma ń ṣáájú nínú eré tí àwọn tókù yóò sì ma kọ́wọ̀ọ́ tẹ̀le bákan náà ni àw...
ìyá ìlù ìyá ìlù ìyá ìlù jẹ́ ìlù ilẹ̀ adúláwọ̀ tí wọ́n gbẹ́ gẹgẹ́ bí dígí tí wọ́n fi ń ka wákàtí láyé àtijọ́ pàáv pàábjùlọ ní lẹ̀ yorùbá wọ́n ma ń fi ìyá ìlù sọ̀rọ̀ gẹ́gẹ́ bí eni wípé ènìyàn ni ó ń sọrọ̀ nígbà tí wọ́n bá lo ìwọ́hùn ènìyàn láti fi lu ìlù náà ìrísí rẹ̀ wọ́n gbẹ́ gẹgẹ́ bí dígí tí wọ́n fi ń ka wákàtí láyé à...
ìlù omele omele jẹ́ ẹ̀yà ìlù kan tí ó wópọ̀ ní ilẹ̀ adúláwọ̀ àwọn ẹ̀yà awúsá gúsù ilẹ̀ nàìjíríà ni ó ni ìlù náà omele jẹ́ ìlù olójú mẹ́ta tí wọ́n máa ń fi igi lù
ìlù gúdúgúdú omele jẹ́ ẹ̀yà ìlù kan tí ó wópọ̀ ní ilẹ̀ adúláwọ̀ àwọn ẹ̀yà awúsá gúsù ilẹ̀ nàìjíríà ni ó ni ìlù náà
ìlù àgídìgbo àgídìgbo jẹ́ ohun èlò orin ìbílẹ̀ tí ìrísí rẹ̀ dàbí dùrù piano àwọn gẹ̀ẹ́sì àwọn yorùbá tí wọ́n ma ń fi okùn sí láti lè gbe kọ́rùn fún lílù lásìkò tí wọ́n bá fẹ̀ dára wọn lára yá alágìídìgbo náà yóò wọ òrùka tó lúpọn ọrùn ìṣà tábí ìgò sọ́wọ́ àtànpàkò rẹ̀ 3yí tí yóò fi ma kan ẹ̀gbẹ pátákó àgídìgbo náà yóò s...
folu storms ada foluwake ogunkeye ti a npe ni folu storms jẹ olugbesi redio ti nijeriya kan ati olukọni oṣere oluṣere olorin-orin ati alagbasi iṣẹlẹ
funsho williams anthony olufunsho williams oṣu karun ojo kesan 1948 - oṣu keje 27 2006 je oloselu lati ipinle eko ati oludari alakoso labẹ isakoso ologun ti ile-igbimọ colonel olagunsoye oyinlola ni lagos funsho williams lọ si ile-iwe st paul's catholic ni ebute metta ati lẹhinna st gregory's college lagos ni ọdun 1968...
funsho adeolu funsho adeolu tí a bí ní ọjọ́ kẹ̀sán-án oṣu kàrún ún ọdún 1968 jẹ́ òṣèré sinimá-àgbéléwò olùdarí àti olóòtú ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà ìgbé-ayé ni ìgbà èwe wọ́n bí fúnnṣọ́ adéolú lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù karùn-ún ọdún 1968 ni ìpínlẹ̀ oǹdó lórílẹ̀ èdè nàìjíríà ó kàwé àkóbẹ̀rẹ̀ ní baptist academy ó kàwé gboyè gíga ...
olusola obada olusola obada ti a bi olusola idowu agbeja ni june 27 1951 jẹ oloselu ati amofin naijiria nipa iṣẹ o wa bi igbakeji gomina ti ipinle osun lati ọdun 2003-2010 gẹgẹbi minisita fun ipinle idaabobo lati ọdun 2011-2012 ati lẹhinna gẹgẹbi minisita minisita idaabobo lati ọdun 2012-2013 labẹ igbimọ ti aare goodlu...
thomas adeoye lambo thomas adeoye lambo obe march 29 1923 - march 13 2004 je omowe naijiria olusakoso ati psychiatrist a kà ọ gẹgẹbi akọkọ akọṣẹmọ-ara-o-ni-ni- oorun ti o wa ni orilẹ-ede naijiria ati afirika
olusegun olutoyin aganga olusegun olutoyin aganga ti a bi ni odun 1955 je minisita fun iṣẹ iṣowo ati idoko ti najiriya aganga ti ni iyawo to oje abiodun aganga née awobokun o ni awọn ọmọ mẹrin oun tun jẹ anor si gomina ti iṣaaju ti kwara state salaudeen latinwo
oluseyi petinrin air chief balogun oluseyi petinrin bi 19 january 1955 je are oṣiṣẹ nigerian air force ati ogagun tele oloye ti olugbeja oṣiṣẹ igbesi aye tete petinrin lọ si ile -iwe giga ti ijọba federal sokoto
bolatito *aderemi-ibitola
2019 lagos state gubernatorial election awọn idibo aṣoju 2019 ti eko ni yoo waye ni oṣu kẹta ọjọ kesan ti a ti firanṣẹ sẹhin lati oṣu keji lati yan gomina ti ipinle eko idibo naa yoo waye ni asiko kan pẹlu orisirisi awọn idibo orilẹ-ede ati ti ipinle
babajide sanwo-olu babájídé olúṣọlá sanwó-olú ojoibi jẹ́ olóṣèlú àti gómìnà ìpínlẹ̀ èkó to wà lórí àléfà lọ́wọ́́lọ́wọ́ wọ́n dìbò yàán- gẹ́gẹ́ bí gómìnà ìpínlẹ̀ èkó ní ọdún 2019 lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú apc lẹ́yìn ti gomina àná ìpínlẹ̀ eko akinwunmi ambode jakule ninu idibo abele egbe all progressive congress = ètò ẹ̀kọ́ ...
jìmí agbájé olújìmí kọ́láwọlé agbájé tí à ń pè ní jìmí agbájé tí a bí ní ọjọ́ kejì oṣù kẹta ọdún 1957 march 2 1957 jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ olóògún òyìnbó àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà ó díje dú ipò gómìnà ìpínlẹ̀ èkó ní ọdún 2015 àti 2019 lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́-òṣèlú people's democratic ṣùgbọ́n ó pàdánù gbogbo rẹ̀ ìgbà èwe à...
segun agbaje segun agbaje ti a bi ni ọdun 1964 ni oludari alakoso ti gtbank ile-iṣẹ iṣowo ti orilẹ-ede naijiria kan o tun jẹ oludari ti ati ọmọ ẹgbẹ ti advisory board aaarin-ila oorun ati afrika ẹkọ segun agbaje lọ si awon ile iwe obalende ipinle eko nigeria ati kent england fun eto-ẹkọ giga rẹ lẹhinna o tẹsiwaju si ca...
femi hamzat dokita kadri obafemi hamzat ti a mọ ni femi hamzat jẹ igbakeji gomina ipinle eko fun gomina babajide olusola sanwo-olu won dibo yan obafemi hamzat pelu gomina sanwo-olu ni odun 2019 labe asia egbe-oselu all progressives congress apc obafemi hamzat ti fi igba kan je komisona fun eto-ise no ipinle eko ni akok...
davido david adédèjì adélékè tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ davido tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kọkànlá ọdún 1992 november 21st 1992 jẹ́ gbajúmọ̀ olórin ìgbàlódé ọmọ bíbí ìlú ẹdẹ ní ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun lórílẹ̀ èdè nàìjíríà davido gba àmì ẹ̀yẹ next rated award ni ọdun 2012 ni à kó jo “the headies ní èyìn ìgbà tí o kọ orin ...
mogbue famely
monsoro monsoro jẹ ọkan ninu awọn abule julọ ti fránsì ni ọdun 2000 ilu monsoro ni akojọ si bi ajogunba aye nipasẹ unesco gẹgẹbi apakan ti afonifoji loire awọn ẹda-ara iwewewe ti idagbasoke ilu ni monsoro<br></small>
bisoye tejuoso olóyè bísóyè tẹ́júoṣó jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà láti ìlú abẹ́òkúta a bí sínu ẹbí tẹ́júoṣó ni ilẹ̀ ẹ̀gbá tí ó sì jẹ́ olórí àwọn obìnrin ní abẹ́òkúta àti iyálóde ní ìlú ẹ̀gbá pátá pátá
tara fela-durotoye tara fẹlá-durotoye 6 march 1977 jẹ́ alatike oge ati amofin ọmọ ilẹ̀ naijiria oluso-aṣáájú ninu iyawo iṣẹ-ọṣọ lati orile-ede naijiria o gbe iṣelọpọ igbeyawo ni akọkọ ni 1999 ṣeto awọn ile-iṣẹ iṣọye ti ilu okeere ati iṣeto ti akọkọ ile-iwe giga ni nigeria
joke silva jọkẹ́ silva 29 september 1961 jẹ́ òṣèré àti olùdarí ọmọ orílẹ̀-èdè ilẹ̀ nàìjírìà ó lọ sí ilé-ìwé fásitì tìlú èkó àti fásitì webber douglas academy of dramatic art ní ìlú lọ́ndọ̀nùó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ fíìmù ṣíṣe ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 1990 ní ọdún 1998 ó kó ipa pàtàkì nínú fíímù colin firth àti nia long ní àwùjọ british-ca...
nike oshinowo nike oshinowo ti a npe ni adenike asabi oshinowo 1966 - tun ti sọ bi nike oshinowo-soleye - jẹ olukọni ile agbowoja oludari alakoso ati aami-ara laati ilu naijiria
natasha akpoti natasha akpoti jẹ́ agbẹjọ̀ró àti óṣélù ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjírìa natasha gbé àpotí fún ilé-ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ ọmọ social democratic party
lisa folawiyo lisa folawiyo jẹ onise apẹẹrẹ aṣaju ilu naijiria kan pẹlu itọkasi lori idinku ati fifọ sequin igbesiaye lisa folawiyo ka iwe amofin ni yunifasiti ti lagos lisa folawiyo bẹrẹ aami rẹ jewel by lisa ni odun 2005 lati ile rẹ igbesi aye ara ẹni folawiyo je iyawo fun akande folawiyo ti baba re je wahab iyanda f...
toyosi akerele-ogunsiji toyosi akerele-ogunsiji wọ́n bí oluwatoyosi akerele ní ọjọ́ kẹ́jo oṣù kọkànlá ọdún 1983 ó jẹ́ alákòóso àwọn olókoòwò-aládáni ti ìlu nàìjíríà àti ọnímọ̀ nípa ìdàgbàsóke àwọn ènìyàn tí ọwọ́ ìja rẹ̀ lọ jákèjádò okoòwò-aládáni ètò-ẹ̀kọ́ ìdàgbàsókè àwọn ọ̀dọ́ àti ìdarí ìlú ó jẹ́ olùdásílẹ̀ àti alákòó...
bilikiss adebiyi abiola bilikiss adebiyi tabi bilikiss adebiyi abiola jẹ́ ́ ọmọ nàìjíríà aláṣẹ iléeìsọstí-dọ̀tun wecyclers ní ìlú èkó lagos - based recycling company wecyclers ó gbàgbọ̀ pé ẹ̀kọ́ ẹlẹ́kọ́ ni ẹ̀gbà ẹlẹ́gbà tòun ti iléeṣẹ́ rẹ̀ ti gba àmì-ẹ̀yẹ púpọ̀ lára wọn ni ẹ̀bùn king baudouin international development ...
gulzar group of institutes gulzar group of institutes jẹ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga ní khanna ìlú ludhiana ní orílẹ̀ èdè india ilé ẹ̀kọ́ yii jẹ́ ti aladani ó sì wà ní abẹ́ ilé ẹ̀kọ́ ti ìjọba punjab technical university jalandhar
yuri andropov yuri vladimirovich andropov je oloselu soviet kan ati akowe agba ti party partyist ti soviet union
leonid brezhnev leonid ilyich brezhnev je oloselu soviet kan ati akowe agba ti party partyist ti soviet union
konstantin chernenko konstantin ustinovich chernenko je oloselu soviet kan ati akowe agba ti party partyist ti soviet union
georgy malenkov georgy maximilianovich malenkov je oloselu soviet kan ati akowe agba ti party partyist ti soviet union
ronke ademiluyi ronke ademiluyi jẹ́ onímọ̀ àṣà àti oníṣòwò kan ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà aye ọmọ-ẹkọ giga ti ofin ademiluyi ni a bi ni england united kingdom ṣugbọn o jẹ ifasalẹ ile-ife ni ipinle osun o ni oludasile oṣoogun aṣayan afirika iṣẹ akanṣe ti o nse igbelaruge awọn apẹẹrẹ afanifoji afirika nipasẹ awọn ẹka rẹ agba...
jackie aina jackie aina august 4 1987 jẹ ẹwa amerika kan youtuber o ṣe onigbagbo fun iwoye ti awọn ọmọ amẹrika-amẹrika ni ile-ọṣọ o ti ṣe alabaṣepọ pẹlu elf kosimetik idojukọ sephora ati sigma beauty awọn awards ni /https//enwikipediaorg/wiki/49th_naacp_image_awards 49th naacp image awards lori january 15 2018 aami gba...
nike akande onikepo olufunmike akande oon con bi onikepo olufunmike adisa ni 29th october 1944 ni lagos nigeria jẹ oṣowo aje oniṣiro ati onisẹ - ọrọ kan ti orile-ede naijiria ti o ṣiṣẹ bi aare ile- iṣẹ lagos chamber of commerce and industry ati igbakeji alakoso olori orile-ede naijiria ti awọn ile-iṣẹ ti okoowo ile-iṣẹ...
natasha apkoti
omoyemi akerele omoyemi akerele ni oludasile ati oludari alakoso style house files ile-iṣẹ iṣowo-owo iṣowo omoyemi lọ si yunifasiti ti lagos nibi ti o ti gba oye oye ni ofin o tẹsiwaju lọ si yunifasiti ti warwick ni ibi ti o ti gba oye oye ni economic economic economic o ṣiṣẹ ni olaniwun ajayi ni ile-iṣẹ ti ilufin ati ...
omowunmi akinnifesi akinnifesi omowunmi jẹ oṣowo oniṣowo kan ni orile-ede naijiria ati aṣoju ayika fun ile eko early life and education ọmọbìnrin ti oludari akọkọ bank bank of nigeria akinnifesi ni a bi ni lagos sugbon o lo awọn ọdun atijọ ni sierra leone ṣaaju ki o to pada si ilu naijiria pẹlu awọn ẹbi rẹ o lọ si ile-...
bunmi banjo bunmi banjo jẹ alakoso iṣowo bii onibara tita ati oniṣẹ imọran pẹlu iṣẹ ti o n ṣalaye ọpọlọpọ awọn iṣẹ awọn wọnyi ni awọn iṣẹ awujo epo ati gaasi awọn iṣẹ iṣowo ati imọ-ẹrọ bunmi jẹ lọwọlọwọ fun google ati atunṣe ni afirika