raw_text
stringlengths
2
128k
10 hygiea 10 hygiea àmì-ìdámọ̀ jẹ́ pálánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì
plánẹ̀tì
mẹ́rkúríù plánẹ̀tì
tunde kelani nigerian filmmaker túndé kèlání ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 1948 born 26 february 1948jẹ́ gbajú gbajà olùgbéré jádeayàwòrán adarí eré àti onímọ̀ nípa sinimá ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ni tk ohun tí tk mọ̀ọ́ṣe ju ni kí ó gbe eré tí ó polongo àṣà àti ìṣe yorùbá tí ó nítàn...
tọ́lá ọládòkun ọwọ́mitọ́lá oládòkun tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí ìka lọmọ ejò jẹ́ gbajú gbajà òṣèré orí-ìtàgé yorùbá ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà wọ́n bi ní ìlú ìgàngàn tí ó jẹ ọ̀ was ọ̀kan lára àwọn ìlú ìbàràpá méjèèjé ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti ti girama ní ilé-ẹ̀kọ́ methodist primary school tí ó wà n...
adébáyọ̀ tìjání adébáyọ̀ tìjání tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹta ọdún 1975 jẹ́ gbajúgbajà olóòtú olùdarí àti òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí agbolé alubàtá ní ìlú ọ̀yọ́ lórílẹ̀-èdè nàìjíríà ọdún 2002 adébáyọ̀ tìjání ti kọ tí ó sìn ṣe olóòtú sinimá àgbéléwò rẹ̀ tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní dúrósinmí lẹ́yìn èyí onírúurú ...
iṣu ewùrà iṣu ewùrà tàbí abo iṣu tí wọ́n pè ní dioscorea alata jẹ́ ẹ̀yà iṣu tí ó yatọ̀ sí àwọn ẹ̀yà iṣu tókù nípa fífà bí ilá tí óa ń fà nígbà tí wọ́n bá rin-ín ó sábà ma ń ní awọ̀ olómi aró sí lavender nígbà tí wọ́n bá haá làì tii bẹẹ́ ìwúlò rẹ̀ àwọn yorùbá ma ń fi iṣu yí dárà oríṣiríṣi bí kí wọ́n fi se àsáró díndín ọ...
àsáró àsáró jẹ́ orúkọ àpapọ̀ fún irúfẹ́ oúnjẹ tí a sè pẹ̀lú àwọn èròjà oríṣiríṣi sè papọ̀ lẹ́ẹ̀kan náà oríṣiríṣi àsáró lò wà nílẹ̀ yorùbá àsáró iṣu àsáróànàmọ́ àsáró kókò àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọèyíkéyìí nínú àsáró tí wọ́n bá sè ni wọ́n máa ń kó ohun èròjà onírúurú papọ̀ láti fi pèsè oúnjẹ aládìídùn yìí àsáró jẹ́ oúnjẹ tí ọ̀...
imamuddin punjabi indian islamic scholar abu al-fadhl imāmuddīn khān barāwli chhachhrī tí a tún mò sí imamuddin punjabi ó kú ní 1916 jé indian ti mùsùlùmí sunni onímò ìjìnlè tí ó se olùdásílè jamia miftahul uloom ìtàn ìdílé àwon asááju imāmuddīn punjabi wá láti agbègbè brawl bajaur wón ti sí lo sí chhachh wón sì se ibù...
tehzeeb-e-niswan tehzeeb-e-niswan ni èdè urdu تہذیبِ نسواں jẹ iwe irohin ti ẹsin musulumi ọsọsẹ fun awọn óbinrin ti sayyid mumtaz ali ati iyawoó rẹ muhammadi begum da kalẹ ni ọdun 1898 èyi jẹ iṣẹ akọkọ to da lori ẹtọ awọn óbinrin ni islam wọn tẹ jade lati ilẹ lahore ni aarin ọdun 1898 ati 1949 ìtan tehzeeb-e-niswan sye...
minnatullah rahmani indian sunni muslim scholar minnatullah rahmani ni wọn bini ọjọ kèjè óṣu april ọdun 1913 ọjọ ògun óṣu march ọdun 1991 jẹ́ ónimọ ẹsin musulumi sunni ti ilẹ india to jẹ akọkọ gbogbo akọwé ti igbimọ aladani ófin ti gbógbó musulumi ilẹ india arakunrin naa jade ni darul uloom nadwatul ulama ati darul ulo...
yaseen akhtar misbahi yaseen akhtar misbahi ọdun 1953 ọjọ kèjè óṣu may ọdun 2023 jẹ ónimọ ẹsin musulumi sunni sufi ati onise iroyin to ni ibaṣèpọ pẹlu raza academy ti ilẹ india arakunrin naa jẹ igbakeji piresidenti ti igbimọ ofin fun gbógbó musulumi ilẹ india ati àlaga ti majlis-e-mushawarat fun gbógbó musulumi ilẹ ind...
muhammadi begum islamic scholar muhammadi begum tí a tún mò sí sayyidah muhammadi begum 22 may 1878 2 november 1908 ó jé onímò ìjìnlè mùsùlùmí sunni sunni muslim ònkòwé urdu àti alágbàso fún èkó obìnrin ó se àjodásílè ìwé ìròhìn òsè ti mùsùlùmí tí a mò sí tehzeeb-e-niswan tí ó sì jé olóòtú olùdásílè ìwé ìròhìn náà ó jé...
hamid al-ansari ghazi hāmid al-ansāri ghāzi ọdún 1909 sí 16 oṣù kẹ́wàá ọdún 1992 jẹ́ ọ̀mọ̀wé mùsùlùmí ará ìlú india kan òǹkọ̀wé àti oníṣẹ́ ìròyìn tí ó dá nadwatul musannifeen tí ó sì ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olóòtú ìwé ìròyìn madinah ọlọ́sẹ̀-méjì ó jẹ́ ọmọ muhammad mian mansoor ansari àti ọmọ ilé-ìwé ti darul uloom deoband jami...
hakeem muhammad akhtar hakeem muhammad akhtar ọdún 1928 sí ọjọ́ kejì oṣù kẹfà ọdún 2013 jẹ́ ọmọwé mùsùlùmí sunni ará ìlú pakistan akéwì onínúure àti olùdámọ̀ràn sufi ó dá jamiah ashraful madrāris sílẹ̀ ní karachi ó jẹ́ ọmọ ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìpínlẹ̀ unani medical college allahabad àti madrasa bait-ul-uloom sarai mir ó j...
zafeeruddin miftahi indian mufti zafeeruddin miftāhi ọjọ kèjèóṣu march 1926 ọjọ ọkan lèèlọgbọn óṣu march 2011 jẹ onimimọ ẹsin musulumi ati adajọ ilẹ india to jẹ mufti of darul uloom deoband ati arẹ̀ keji fun ilẹ kewu ti fiqh arakunrin naa ṣè akójọ ofin ẹsin ti azizur rahman usmani ta n peni fatāwa darul uloom deoband n...
bonny estuary bonny estuary tabi bight of bonny je estuary kan ni etikun ipinle rivers nigeria nitosi port harcourt o jẹ apakan ti delta river river ilẹ̀ náà jẹ́ àkóso pápá swamp mangrove tí ó jọra nínú àwọn ewéko pẹ̀lú agbègbè esturine ní niger delta ara omi inu ile pataki kan wa lẹhin agbegbe igberiko port harcourt t...
goliath aramada onyebuchi goliath jẹ aramada itan-akọọlẹ imọ-jinlẹ ọdun 2022 nipasẹ onkọwe ara ilu amẹrika amẹrika tochi onyebuchi o jẹ aramada itan-akọọlẹ imọ-jinlẹ agbalagba akọkọ rẹ ati pe o ti tẹjade ni ọjọ 25 oṣu kini ọdun 2022 nipasẹ tor books abẹlẹ ninu ifọrọwanilẹnuwo nipasẹ npr onyebuchi sọ ọpọlọpọ awọn fiimu ...
igbesi aye mi ninu igbo ti awọn ẹmi aramada my life in the bush of ghosts jẹ aramada lati ọwọ onkọwe ọmọ orilẹ - ede naijiria amos tutuola ti a ṣejade ni ọdun 1954 lẹ́yìn tí ó ti sá fún àwọn oníṣòwò ẹrú pẹ̀lú ẹ̀gbọ́n rẹ̀ a ṣe afihan aramada naa gẹgẹbi ikojọpọ awọn itan-akọọlẹ ti o jọmọ botilẹjẹpe kii ṣe nigbagbogbo ni ...
askimam askimam jẹ́ ojú-òpó wẹ́ẹ̀bù tí ń pèsè àlàyé nípa ẹ̀sìn mùsùlùmí ọ̀mọ̀wé nípa ẹ̀kọ́ mùsùlùmí kan tó jẹ́ ọmọ south africa àti adájọ́ kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ ebrahim desai ló ṣe ìdásílẹ̀ ojú-òpó yìí ní ọún 2000 àwọn ìdáhùn orí ojú-òpó yìí jẹ́ àfihàn òfin nípa ìwòye hanafi deobandi ó ti ní ipa rẹpẹtẹ ó sì gbajúmọ̀ j...
olayemi cardoso olayemi micheal yemi cardoso jẹ́ ọmọ nigeria òṣìṣẹ́ àgbà ilé-ìfowópamọ́ oníṣòwò-àgbà ìpín-ìdókòwò àti òní-lámèyító ètò àwùjọ tí ààrẹ bola ahmed tinubu ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn láti di gómìnà ilé-ìfowópamọ́-àpapọ̀ lọ́jọ́ 15 - 09 - 2023 ó ti fìgbà kan jẹ́ alága ilé-ìfowópamọ́ citibank ní nigeria bẹ́ẹ̀ náà ló ti jẹ kọmí...
hakeem effects nigerian special effects artisthakeem effects tí orúkọ àbísọ rẹ̀ jẹ́ hakeem onilogbo ajibola jẹ́ amójú ẹni gúnrégé fún àwọn eléré nollywood tí ó sojúdé àwọn èyí tó dá yàtọ̀ níbi ka fojú ẹni dárà ó jẹ́ olùdásílẹ̀ àti olùdarí tricks international tí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tó ń fojú ẹni dárà tí ó sì ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ...
arne kaijser arne kaijser ti a bi ni 1950 jẹ olukọ ọjọgbọn ti itan-akọọlẹ ti imọ-ẹrọ ni kth royal institute of technology ni dubai ati alakoso titele ti awujọ fun itan imọ-ẹrọ kaijser ti ṣe atẹjade awọn iwe meji ni swedish stadens ljus 'etableringen av de första svenska gasverken ati 'i fädrens spår' den svenska infras...
guido borelli guido borelli da caluso jẹ oluyaworan ilu italia a bi ni caliso ni ọdun 1952 o wa lati ipilẹṣẹ iṣẹ ọna ati pe ẹbi rẹ nigbagbogbo gba ọ niyanju lati ṣe idagbasoke talenti rẹ ni kutukutu bi igba ewe o ṣẹgun idije kan ni ọdun metala o si ṣe ifihan akọkọ rẹ ni ọjọ-ori ọdun metadinlogun ni ars plauda galleri n...
davoud soleymani davoud soleymani داوود سلیمانی je oloselu ara iran soleymani jẹ igbakeji minisita fun ọran awọn ọmọ ile-iwe ni ile-iṣẹ ti imọ-jinlẹ iwadi ati imọ-ẹrọ labẹ minisita ti minisita tẹlẹ mostafa moin </link> o tun jẹ aṣoju lati tehran ni akoko kẹfa ti ile-igbimọ islam islam iran majlis
ájálù to ṣẹ̀lẹ nipa ìfómipamọ ti gusau ìfómipamọ ti gusau ni ìfomipamọ to wa ni ódó sokoto ni apa oke lati gusau ólu ipinlẹ zamfara ni órilẹ ede naijiria ìfómipamọ naa pin omi fun awọn ilù ati àgbègbè ipinlẹ naa ni ọdun 2006 ìfómipamọ naa ṣubù eyi lo fa iku awọn èniyan ógóji ati iparun ile ti ẹẹdẹ̀gbẹta gbigbẹ ìfómipam...
omo ghetto omo ghetto jẹ́ fíìmù àgbéléwò apanilẹ́rìn-ín ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2010 olùarí fíìmù náà ni abiodun olarenwaju àwọn òṣèré tó sì kópa nínú fíìmù náà ni funke akindele bimbo thomas ireti osayemi esther kalejaiye àti eniola badmus àhunpọ̀ ìtàn fíìmù náà dá lórí àwọn ìwà búburú lóríṣiríṣi tó wà ...
bimbo thomas bimbo thomas jẹ́ òṣèrẹ́bìnrin ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti aṣàgbéjáde fíìmù ó sì tún jẹ́ oníṣòwò ìgbésí ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí bimbo thomas sí ìpínlẹ̀ èkó sínú ìdílé elénìyàn méje ó gba àmì-ẹ̀yẹ nínú ẹ̀kọ́ creative arts láti university of lagos iṣẹ́ tó yàn láàyọ̀ bimbo bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré gẹ́gẹ́ bí i ak...
nancy isime nancy isime tí wọ́n bí ní ọjọ́ 17 oṣù december ọdún 1991 jẹ́ òṣèrébìnrin àti oníṣẹ́ orí ẹ̀rọ-ayélujára tí orílẹ̀-èdè naijiria early life and background ìpínlẹ̀ ẹdó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà lọ́ bí nancy isime sí sínú ẹbí tó wá láti ìran esan lẹ́yìn tó parí ẹ̀kọ́ girama ní benin city ó lọ sí university of lagos...
déyẹmí ọ̀kánlàwọ́n
the wedding party
alex ekubo alexx ekubo tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ alex ekubos-okwaraeke tí wọ́n bí ní ọjọ́ 10 oṣù april ọdún 1986 jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà óun ló gbégbá orókè nínú ìdíje mr nigeria tó wáyé ní ọdún 2010 ó gba àmì-ẹ̀yẹ best actor in a supporting role ní 2013 best of nollywood awards fún ìkópa rẹ̀ nínú weekend...
leon balogun leon aderemi balogun tí wón bí ní 28 june 1988 je agbaboolu-elese omo orilede naijiria ti a bi si orilede jẹ́mánì o je adi eyin mu fun egbe agbabolu balogun ti gba boolu fun iko agbaboolu a ti seyin egbe agbaboolu balogun ko pa takun-takun fun ìgbà àkókó ninu egbe idije ni ojo kokandinlogun osu igbe odun 2...
dele alli bamidele jermaine alli / ˈd ɛ l i ˈ æl i / del -ee al -ee ti a bi 11 oṣu kẹrin ọdun 1996 jẹ agbabọọlu adi arin mu ara ilu gẹẹsi ti o n gba boolu ninu idije premier league pelu iko ẹgbẹ agbabọọlu everton dele gba boolu fun england u17 u18 ati u19 ṣaaju gbigba boolu pelu egbe agba orilede naa ni ọdun 2015 o kop...
joel marangella joel marangella jẹ oboist ara ilu amẹrika kan ti o ti ṣe ere pẹlu ọpọlọpọ awọn akọrin olorin agbaye ọmọ ẹgbẹ ti o ṣẹda ti speculum musicae o jẹ oboist akọkọ fun west australian symphony orchestra ati ọmọ ẹgbẹ ti o ṣẹda ti ẹgbẹ orin tuntun igbesiaye a bi marangella ni washington dc o kọkọ kọ eko faranse ...
akpan hogan ekpo akpan hogan ekpo listen ojoibi 26 okufa 1954 je onimo-okowo ati ojogbon omo naijiria lọ́wọ́lọ́wọ́ ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nípa ètò ọrọ̀ ajé àti ètò ìgbòkègbodò ní yunifásítì ti uyo ìpínlẹ̀ akwa ibom nigeria ekpo tun jẹ alaga ti foundation for economic research and training fert ni lagos nigeria oun ni oludari...
ìgbimọ apapọ lori àyipada óju ọjọ ìgbimọ apapọ lori àyipada òju ọjọ jẹ ajọ apapọ to da lori pipa àṣẹ lori ayipada óju ọjọ ati ipa rẹ ni órilẹ ede naijiria ìgbimọ yii ni a da silẹ ni ọdun 2022 labẹ akósó arẹ tẹlẹ ri muhammadu buhari lati da ófin kalẹ lori iranlọwọ bi ọrọ ajè ilẹ naijiria ṣè maa dàgbàsóke ni ọdun 2022 ar...
deoband town in uttar pradesh india deoband jẹ́ ìlú kan tí ó ní ìjọba ìbílẹ̀ tirẹ̀ ní agbègbè saharanpur ní ìpínlẹ̀ uttar pradesh india nípa bíi 150 km láti delhi darul uloom deoband ilé-ẹ̀kọ́ islam àti ọ̀kan nínú àwọn ilé-ẹ̀kọ́ islam tí ó tóbi jùlọ ti india wà níbẹ̀
deobandi movement sunni revivalist movement deobandism túndarí síbí yìí fún the political ideologies associated with it ẹ wo islamism ẹgbẹ́ deobandi tàbí deobandism jẹ́ ẹgbẹ́ ìsọjí láàárín sunni islam tí ó faramọ́ ilé-ìwé òfin hanafi ó ṣẹ̀dá ní ìparí ọ̀rúndún ọ̀kàn-dín-lọ́gún ní àyíká madrassa darul uloom ní deoband in...
j j abrams american filmmaker born 1966 jeffrey jacob abrams a bíi ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1966 jẹ oṣere ati olupilẹṣẹ ara ilu amẹrika kan o jẹ olokiki julọ fun awọn iṣẹ rẹ ni awọn oriṣi iṣe eré ati itan-akọọlẹ imọ-jinlẹ action drama àti science fiction abrams kọ̀wé ó sì ṣe àgbéjáde irú àwọn fíìmù bíi reg...
asghar hussain deobandi indian sunni islamic scholar asghar hussain deobandi ti atun lè pé ní mian sayyid asghar hussain 16 october 1877 — 8 january 1945 je akeko gboyè ni imọ mùsùlùmí indian sunni ó pelu awon oludasile madrasatul islah àbí ni ojo kẹrin dín lógún ọsu kẹ̀wá ọdún 1877 sì ìdí ilé deoband ojewo olóòótọ́ èn...
ìṣilọ ati àyipada lori àyika ágbàyè ìṣilọ ati àyipada lori àyika ágbàyè jẹ ìwadi nipa ipa ti ayipada óju ọjọ kó ninu ìṣilọ ọmọ èniyan ati iṣikuró ni wọn tẹ si ta ni ọdun 2011 iwadi yii wa lati ẹka èró ni àbẹ àkósó ijọba uk to da lori imọ ijinlẹ̀ eyi ni wọn pe ni èró iroyin larin awọn ti oun ṣiṣẹ ni abẹ ójù ọjọ ati ìṣil...
gaia zucchi gaia zucchi ojoibi march 27 1970 je osere ara itálíà
akah nnani nigerian actorakah nnani jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà olóòtú èò lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán àti òṣìṣẹ́ orí youtube ó gbajúmọ̀ fún ìkópa rẹ̀ nínú fíìmù àgbéléwò banana island ghost èyí tó mu kí wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnlá àti ìkẹẹ̀ẹ́dógún ti the ama awards fún òṣèrékùnrin tó dára jù ní ọdún 2...
ilerioluwa oladimeji aloba mohbad ilerioluwa oladimeji aloba tí ìnagijẹ rẹ̀ ńjẹ́ mohbad tàbí ìmọ́lẹ̀ wọ́n bíi ní 3 oṣù kìn-ín-ní ṣẹẹrẹ ọdún 1996 ó dágbére fáyé ní 12 oṣù kẹsán ọ̀wẹ́rẹ́ ọdún 2023 ó jẹ́ akọrin tàkasufe ati aṣàpílẹ̀kọ́-orin ó jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ èkó ó kọ́ n gbé orin síta pẹ̀lu àtìlẹ́hin ilé iṣẹ́ ìgbórin ...
aarun ómi ati àyipada óju ọjọ àyipada óju ọjọ lo ti fa óriṣiriṣi itankalẹ ààrun ati ailèra papa èyi to farapẹ ti ómi ìpa àyipada óju ọjọ lo ti wa kakiri àgbàye ninu ọgbẹlẹ ikun ómi ójó rirọ to lagbàrà ati ómi to lọwọrọ eyi lo fa aàrun omi to si tu bọ pọsi kakiri ààgbàyè àlèkun ótutu ati iyipada ninu ójó mu ki ààrun ómi...
aarun óri ómi ati àyipada óju ọjọ
ipà àyipada óju ọjọ ninu ẹkọ ọgbin effects of climate change on agriculture ìpa àyipada óju ọjọ ninu ẹkọ ọgbin ti jasi èrè ókó kèkèrè ati onjẹ iyè nitori ọgbẹlẹ óoru igbi ati ìkun ómi eyi lo fa alèkun ba ajẹnirun ati ààrun ohun ọgbin ìpa lati àyipada àpẹrẹ́ óju ọjọ ayipada ninu óju ọjọ ko ipa ninu àgbègbè fun iṣẹ àgbẹ ...
adébáyọ̀ sàlámì
yínká quadri
weekend getaway weekend getaway jẹ́ fìímù ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2012 desmond elliot ni olùdarí fììmù àgbéléwò yìí àwọn òṣèré tó kópa nínú rẹ̀ ni genevieve nnaji ramsey nouah monalisa chinda ini edo uti nwachukwu alex ekubo bryan okwara beverly naya àti uru eke wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ mọ́kànlá ó sí pad...
uti nwachukwu uti nwachukwu tí wọ́n bí ní 3 august 1982 jẹ́ òṣèrékùnrin àti olóòtú ètò ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ jara ọ́ wá láti ndokwa aboh kingdom agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ndokwa east ìpínlẹ̀ dẹ́ltà ní nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ uti wá láti ìdílé elénìyàn mẹ́fà ìpínlẹ̀ delta ni ó dàgbà sí ní ughelli ló...
bryan okwara bryan okwara tí wọ́n tún mọ̀ sí ikenna bryan okwara tí wọ́n bí ní 9 november 1985 jẹ́ òṣẹ̀rékùnrin ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà tó wá láti ẹ̀yà igbo ó kópa nínú ìdíje kan tó sì jẹ́ olúborí tó sì tún gba àkọ́lẹ́ mr nigeria ní ọdún 2007
uru eke nigerian actress born 1979uru eke tí wọ́n bí ní october 11 1979 jẹ́ òṣèrèbìnrin ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà àti aṣàgbéjáde fíìmù àgbéléwò ó gbajúmọ̀ fún fíìmù rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ remember meó kópa gẹ́gẹ́ bí i ẹ̀dá-ìtàn obi nínú àwọn fíìmù orí èrọ-amóhùnmáwòrán lórí ndani tv bí i rumour has it last flight to abuja ...
ibiyemi olatunji-bello wón bi olatunji-bello sí agbegbe ogbowo ni idumota ní ípiịnlẹ̀ èkó ninu ìwọ̀ oòrùn tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ órilé èdè naigiria ní ọjọ kẹta lelogun oṣù kẹrin ọdun 1964 o lọ si ile-iwe girama ọdọmọbìnrin anglican ni surulere laarin ọdun 1970 ati 1974 ati ile-iwe giga awọn ọmọbirin mẹtodist ni agbegbe yaba fun ...
ìmúdọ́gba àyipàdà ójú ọjọ́ àṣamubadọgba lori àyipada óju ọjọ jẹ ọna a ti ṣè àtunṣè lori ipa ayipada óju ọjọ èyi jẹ ipa ti oun ṣẹlẹ lọwọ tabi eyi to nbọ àṣamubadọgbà jẹ ọna lati dinku tabi dina abùrù kuró fun ọmọ èniyan èyi jẹ ọnà fun ọpọlọpọ anfani èniyan ni lati dasi ọrọ ayipada ójù ọjọ óriṣiriṣi àgbèkalẹ ati ètó lo w...
tinsel tv series tinsel jẹ́ fíìmù àgbéléwò tí wọ́n máa ń ṣàfihàn lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó bẹ̀rẹ̀ ní oṣù kẹfà ọdún 2008 ní ọjọ́ 23 may ọdún 2013 wọ́n ṣàfihàn 1000th episode eré náà lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán ó jẹ́ fíìmù àgbéléwò orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán tó gbajúmọ jùlọ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ní ọjọ...
zubby michael nigerian actor and movie producer azubuike michael egwu tí a mọ̀ gẹ́gẹ́ bíi zubby michael jẹ́ òṣèré nàìjíríà àti olùgbé eré jáde ó jẹ́ mímọ̀ fún ipa tí ó kó nínú three windows royal storm àti professional lady ìfarahàn rẹ̀ àkọ́kọ́ jẹ́ nínú eré tí a pe àkọlé rẹ̀ ní missing rib ṣùgbọ́n ó jẹ́ mímọ̀ nínú eré ...
samuelle kporaro akpor samuelle kporaro ojoibi december 12 1993 je oluko nigeria ti o ni ba ninu eto oro aje lati yunifasiti ipinle delta ọmọ emmanuelle tun jẹ aṣaaju-ọna ti igbimọ giga ti santeria ti o ni iduro fun atunṣe atunṣe ati aṣoju santeria ẹsin afirika kan ti o ṣe agbekalẹ syncretic ti ipilẹṣẹ yoruba omode a b...
jjc skillz abdulrasheed bello ti a bi 4 kẹrin ọdun 1977 kano ti àwọn ènìyàn mọ sí skillz tabi jjc skillz jẹ akọrin olorin kan ti orilẹ-ede naijiria olorin igbasilẹ ati olupilẹṣẹ fíìmù lórí tẹlifisiọnu jjc skillz ní idanimọ ni nigeria lẹhin ìgbéjáde orin rẹ̀ kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ we are africans èyí tó jẹ́ afrobeats ṣaa...
nonso diobi nigerian actor nonso diobi tí wọ́n bí ní july 17 1976 jẹ́ òṣèrékùnrin tó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó sì tún jé olùdarí fíìmù àgbéléwò lásìkò tó ń kékọ̀ọ́ nípa theatre art ní university of nigeria ó ṣe ìṣàfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ ní ọdún 2001 nínú fíìmù àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ border ...
átẹ́gùn ooru átẹ̀gun óóru jẹ óóru to làgbàrà nigba óju ọjọ gbónà ọriniinitutu giga maa nwa pẹ̀lu átẹ̀gun óóru èyi maa nṣẹlẹ ni órilẹ edẹ pẹlù ójù ọjọ ókun ìwọn átẹgun óórù jẹ ìbàtàn fun ọju ọjọ àgbègbè ati deede otutu fun igba óóru lati àgbègbè awọ̀n eniyan to wa ni ójù ọjọ to gbóna jẹ átẹgun óórù fun awọn ti oun gbè n...
victor olaotan nigerian actor 19522021victor olaotan 17 february 1952 26 august 2021 jẹ́ òṣèré nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ fún ipa tó síwájú tí ó kó nínú soap opera tinsel ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bíi ní ìlú èkó lagos nigeria ní 1952 ó kẹkọọ ní university of ibadan obafemi awolowo university àti rockets university united...
last flight to abuja 2012 nigerian disaster thriller film last flight to abuja jẹ́ fíìmù 2012 nàìjíríà àjálù tí a kọ nípasẹ̀ tunde babalola tí obi emelonye ṣe àti mú jáde tí omotola jalade ekeinde hakeem kae-kazim àti jim iyke ṣe tí a yàwòrán ní ìlú èkó fíìmù náà gba àwọn yíyan àbùn márùn-ún ní ọdún 2013 africa movie a...
ìdajọ lori óju ọjọ ìdajọ lori óju ọjọ da lóri ṣiṣè amujutó ipa àyipadà ójù ọjọ ati imujutó awọn ẹ̀tọ èniyan to farapa nitori ìṣẹ̀lẹ naa awọn ìpènijà idajọ lori ójù ọjọ nigbati awọn àṣofin awọn ọjọgbọn ati iwadi fun imọran ko ba sinibẹ eyi le di atunṣè lori ayipada óju ọjọ ku ìdajọ lori óju ọjọ lèjẹ ọna ati dojukọ awọn ...
funmilola aofiyebi-raimi funlola aofiyebi-raimi tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ abibat oluwafunmilola aofiyebi tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí far jẹ́ òṣèrébìnrin ti orílè-èdè nàìjíríà ó ti ṣàfihàn nínú àwọn fíìmù bí i the figurine tinsel àti mtv shuga ìgbésí ayé rẹ̀ funlola jẹ́ ọmọ àbígbẹ̀yìn àwọn òbí ọlọ́mọ méje ìyá rè jẹ́ onísòw...
matilda obaseki matilda obaseki jẹ́ òṣèrébìnrin àti akọ̀tàn ti orílẹ̀-èdè nàìjíríà òun ni olú ẹ̀dá-ìtàn nínú fíìmù orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ tinsel ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí obaseki ní 19 march 1986 ní benin city ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ oredo ní ipinle edo níbi tí ó dàgbà sí òun ni àbígbẹ̀yìn láàrin ọ...
muhammad ibn muhammad al-fulani al-kishwani muhammad ibn muhammad al-fulani al-kishnawi jẹ́ gbajúgbajà onímọ̀ fúlàní onímọ̀ ìṣirò awòràwọ̀ onímọ̀ nínú èdè lárúbáwá àti amọ̀fin ní sẹ́ńtúrì kejìdínlógún ipinle katsina ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ló ti wá al-kishnawi kẹ́kọ̀ọ́ ní gobarau minaret ní katsina kí ó tó kúrò ní cairo...
ojo maduekwe nigerian politicianchief ojo maduekwe tí wọ́n bí ní ọjọ́ 6 1945 tó sì ṣaláìsí ní ọjọ́ june 29 2016 jẹ́ olóṣèlú orílè-èdè nàìjíríà láti ẹ̀yà igbo ní ohafia ipinle abia ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ó kẹ́kọ̀ọ́ ní university of nigeria nsukka ó sì gboyè ẹ̀kọ́ nínú ìmọ̀ òfin ní ọdún 1972 iṣẹ́ òṣèlú tó yàn láàyò...
muhammad bello muhammadu bello pronunciationi arabic محمد بلو ni sultan keji ti sokoto o si jọba lati ọdun 1817 titi di ọdun 1837 o tun jẹ onkọwe ti nṣiṣe lọwọ ti itan ewi ati awọn ijinlẹ islam o jẹ ọmọ ati oluranlọwọ akọkọ si usman dan fodio oludasile ti sokoto caliphate ati sultan akọkọlakoko ijọba rẹ o ṣe iwuri fun ...
angelo soliman àwọn èdè tí ó sọ soliman sọ àwọn èdè méfà dáradára àti èdè abínibí rẹ kanuri
thomas peters ìgbésí ayé ibẹrẹ thomas peters jẹ bíbí iwọ-oorun afirika sí ẹyà yoruba tí ìlú egba </link> orisun ti ara ẹni ẹrú ní ọdún 1760 ọmọ adulawo tí o jẹ ọmọ ọdún mejilelogun lẹhinna tí a pe ní thomas peters àwọn onísòwò ẹrú tí mu bí ẹrú si faranse louisiana lórí ọ̀kọ̀ ojú omi faranse kan henri quatre ní ìgbà tí ...
làdipó sòlánkè ládípò sólànké c 1886 - ojo keji osu owéwè 1958 jè olósèlú alápon kan tí a bí ní ìlú nàíjíríyà tó se ìpolongo lórí àwon òrò apá ìwò oòrùn adúláwò
dosunmu ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa the oba of lagos fún other people ẹ wo dosunmu surname dosunmu 1823 1885 tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí docemo gẹ́gẹ́ bí ó ṣe wà ní àkọsílẹ̀ ní ìwé ìlú ayaaba ṣe ìjọba rẹ̀ ní ìlú èkó láti ọdún 1853 lẹ́yìn ìgbà tó joyè lẹ́yìn ikú bàbá rè ọba akitoye títí di ìgbà tó fi kú ní ọdún 1885 ó sá lọ sí ìlú...
maitama sule yusuf maitama sule ọjọ́ kìíní oṣù kẹ́wàá ọdún 1929 sí ọjọ́ kẹta oṣù keje ọdún 2017 jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà aláṣejúṣe àti àgbà ìlú tí ó mú ɗanmasanin kano èyí tí ó jẹ́ oyè ìjòyè ní 1955 sí 1956 ó jẹ́ olórí okùn ti ilé-ìgbìmọ̀ aṣojú ti orílẹ̀-èdè ní ọdún 1960 ó darí àwọn aṣojú nàìjíríà sí àpéjọ t...
akpanoluo ikpong ikpong ette akpanoluo ikpong ikpong ette nnom ọjọ́ kẹta-lé-lógún oṣù kẹ́sàn-án ọdún 1929 sí ọjọ́ kẹta-dín-lógún oṣù kẹ́sàn-án ọdún 2018 jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nàìjíríà ti físíksì àti akọ̀wé tẹ́lẹ̀ àti igbákejì ààrẹ ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìmọ̀ sáyẹ́nsì nàìjíríà ní ọdún 1991 ó jẹ́ alákoso ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìmọ̀ sáyẹ́...
christopher oluwole rotimi christopher oluwole rotimi ọjọ́-ìbí ọjọ́ ogún oṣù kejì ọdún 1935 jẹ́ balogun àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ nàìjíríà tó ti fẹ̀yìntì aláṣejúṣe àti olóṣèlú ó ṣiṣẹ́ lásìkò ogun abẹ́lé nàìjíríà ó sì jẹ́ gómìnà àwọn ìpínlẹ̀ ìwọ̀orùn lásìkò tí nàìjíríà wà lábé ìjọba ológun láti ọdún 1971 sí 1975 oluwole rotimi...
gj afọlabi ojo ọjọgbọn gabriel jimọh afọlabi ojo ọdún 1929-2020 jẹ olùkọ́ àti olùdarí ilé ìjọ catholic tí orílẹ̀ nàìjíríà wọn bí arákùnrin náà ni ọjọ àkọ́kọ́ oṣu november ọdún 1929 ni ado-ekiti ilẹ naijiria níbi tó ti ṣe igbiyanju nínú ẹkọ àti ṣiṣẹ́ fún àgbègbè rẹ ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ afọlabi afọlabi bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ ni...
afẹ babalọla nigerian lawyer born 1929 afẹ babalọla con ofr san wọn bíni ọjọ ọgbọn oṣu october ọdún 1929 jẹ agbẹjọro ilẹ naijiria ati oludasilẹ ilé ìwé gíga ti afẹ babalọla ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ afẹ́ babalọlá ni à bisi ipinlẹ ekiti ni gúúsù ìwọ oòrùn ilẹ̀ naijiria arákùnrin náa lọ sí ilé ìwé akọbẹẹrẹ emmanuel ni ado...
gbenga ogedegbe gbenga ogedegbe je dokita naijiria ati ojogbon igbesi aye ni kutukutu ilu eko ni won bi ogedegbe o lo si hussey college warri o pinnu lati di dokita ni omo odun mejo o lo si donetsk national university ati columbia university
colin udoh colin udoh jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ àti olùgbéjáde eré orí tẹlifíṣọ̀n orílẹ̀-èdè nàìjíríà colin n ṣiṣẹ́ lọwọlọwọ fun awọn erẹ́ idaraya kwese o ti ṣe afihan bi oluyanju ile-iṣere fun nẹtiwọọki tẹlifisiọnu super sport ati pe o ti kọwe fun iwe irohin bọọlu afẹsẹgba afirika kick off ó ṣiṣẹ́ fún àjọ agbábọ́ọ̀lù nàìjíríà...
murphy ijemba murphy ijemba jẹ́ òṣèré rédíò ọmọ nàìjíríà tó dá ètò rush hour dúró lórí 977 metro fm oríṣiríṣi ọ̀nà ìkọ́ rédíò rẹ̀ ti jẹ́ kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àyànfẹ́ àti ọ̀wọ̀ fún un níbi ayẹyẹ àmì ẹ̀yẹ ní nàìjíríà igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ igbo ni a bi ni mushin agbegbe kan ni ipinle eko nibiti o ti tẹsiwaju lati pari ẹkọ ile...
josiah sowande josiah sobowale sowande ca 1858 -1936 tí a tún mọ sí sobo arobiodu jẹ́ akéwì ọmọ yoruba àti abeokuta ìpínlẹ̀ ogun tí o jẹ́ olùkọ́we ti ewì ní ara ewì ti o jẹ èdè yorùbá àwọn iṣẹ́ rẹ ni nípasẹ̀ ìdàgbàsókè ní egba àwọn iṣẹ ti christian missionary society ní egbaland àti àwọn orin egba tí o gbajúmò àwọn iṣẹ...
joseph ayo babalola joseph ayo babalola 25 kẹrin 1904 26 keje 1959 jẹ́ mínísítà kristiani ní nàìjíríà àti adarí ijo kristi aposteli tí gbogbo ènìyàn ń pè ni cac ní naijiria àjíhìnréré ìwòsàn ní ihinrere àti ìwòsàn ní 1931 faith tabernacle tí wọn ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú ilé-ìjọsìn àpóstèlì pẹlu ilé-iṣẹ gbògbògbò ni united kin...
gbenga salu oluwagbenga adedoyin salu éni ti á mọ̀ si gbenga salu jẹ́ omo nigerian film director film editor visual effects ati òṣèré o ti bori ati pe o tun ti yan fun ọpọlọpọ awọn ẹbun fun awọn iṣelọpọ fidio orin rẹ o forukọsilẹ fun imọ-ẹrọ mechanical lẹhinna gbe lọ si ẹka ti iṣẹ-ọnà ẹda ni ile-ẹkọ giga ti lagos niger...
kenneth gyang kenneth gyang jẹ́ ọ̀dọ́ tó ń ṣé fíìmù ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí wọ́n sì bí sí barkin ladi ní ìpínlẹ̀ plateau ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó kẹ́kọ̀ọ́ ilé ẹ̀kọ́ fiimu ní national film institute jos ó sì kẹ́kọ̀ọ́ ìkọ̀wé ní gaston kaboré imagine ni ouagadougou burkina faso meji ninu awọn fiimu kukuru rẹ ati iwe afọ...
mallam dendo mallam muhammadu bangana tí a tún mọ̀ sí mallam dendo tàbí manko jẹ́ olókìkí tó gbajúmọ̀ nínú ìtàn ní ọ̀rúndún kọkàndínlógún ní ilẹ̀ nàìjíríà ó jẹ́ ọmọ fulani lati ibi ti a mọ̀ sí ìpínlẹ̀ keb ní òde onibi ti o wa ni ariwa naijiria ni ọrundun kànkàndínlógún nígbàtí agbègbè sudan n ṣe àwọn àyípadà pàtàkì nít...
eze ukwu eze ukwu 17991862 jẹ obi kẹ̀dogún tí ìlú otolo ati igwe ti ijoba nnewi òun ni olórí ati aṣaaju-ẹmi ni nnewi tó jẹ ìlú igbo ni naijiria ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ nnofo royal idile ati arọ́pò bàbá rẹ̀ eze chukwu láìdàbí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọba ilẹ̀ igbo àwọn ọba tí wà ní nnewi kí àwọn ará òyìnbó tó dé
umaru bin ali umaru bin ali 18241891 jẹ sultan sokoto láti 1881 sí 1891 o rọpò sultan mu'azu lẹyin iku rẹ ní oṣù kẹsán 1881 ali jẹ ọmọ ọmọ tí uthman dan fodio ọmọ ọmọ muhammed bello àti ọmọ aliyu babba ali jẹ ọmọ-ọmọ usman dan fodio ṣáájú kí o tó di sultan ali jẹ oyè sarkin sudan o si gbe ni ribat ni ilu shinaka nígbà ...
clarence peters bclarence abiodun peters ti a bi ni 20 oṣu kejila ọdun 1983 jẹ oludari fidio orin naijiria oṣere fiimu ati sinima oun ní oludasile ati alakoso ti awọn aworan ala ala ile-iṣẹ iṣelọpọ kan ti o ṣè amọja ní awọn agbegbe ti awọn iṣẹ ọna ṣiṣe fiimu ati fidio o tun jẹ oludasile ati alakoso ti capital hill reco...
remi vaughan-richards remi vaughan-richards jè oníṣe fíìmù ọmọ nàìjíríà igbesi ayè ibẹrẹ ati ẹkọ a bi remi ní naijiria ọkan ninu awọn ọmọ mẹrin ti a bi si alan richards ayaworan ile gẹẹsi 1925 -1989 ati ayo vaughan 1928-1993 olukọni nọọsi ti o ṣẹda ile-iwe nọọsi ti ipinle eko ayo jẹ lati idile eko olokiki kan ti baba-n...
igwe okafo igwe okafo 18301891 je obi kẹrìndínlógón tí otolo àti igwe tí ijoba nnewi òun ní olórí àti aṣaaju-ẹmi ni nnewi ìlú igbo ni naijiria ó jẹ ọmọ ẹgbẹ́ tí idile ọba nnofo àti arọ́pò bàbá rẹ eze ukwu yàtọ sí ọpọlọpọ awọn ọba igbo àwọn ọ́ba nnewi tí wà ṣáájú kì àwọn òyìnbó tó dé
ejike asiegbu ejike asiegbu // ⓘ</link> jè oṣere fiimu ati oludari fiimu ti orilẹ-ede naijiria ti o jẹ alakoso ẹgbẹ awọn oṣere ti nigeria nigbakan rí o tun ti yan tẹlẹ gẹgẹbi oluranlọwọ ara ẹni fun odumegwu ojukwu ti o jẹ oluranlọwọ fun biafra tẹlẹ lakoko apejọ t’olofin ti orilẹ-ede 1994 ni abuja ẹkọ ejike asiegbu ti k...
mamman nasir nasir mamman gcon ọjọ kejì oṣù july ọdún 1929- ọjọ́ kẹtàlá tí oṣù april ọdún 2019 ni a fún lórúkọ galadiman ti katsina láti ọdún 1992 tí tí de ọdún 2019 jẹ oludajọ ilẹ̀ nàìjíríà tó sìn ilé ẹjọ́ tí arẹ kò tẹmi lọrun láti ọdún 1978 de 1992 ìgbésí ayé mamman nasir mamman ni wọn bí ní ọdún 1929 sì katsina ó já...
mohammed tukur <templatestyles src=moduleinfobox/stylescss></templatestyles> mohammed tukur pr je emir tí kano ìpínlè kan ní ohun tí a n pè ní northern nigeria lóni tukur ní o ṣe olórí kano ní àkókò bassasa àkókò ogún abẹle tí ti o ri òpòlopò awọn tí o ní ẹtọ sí ìtẹ kanoan
orlando martins orlando martins listen 8 december 189925 september 1985 je aṣáájú-ọ̀nà fíìmù àti òṣèré orí ìtàgé yorùbá kan ní nàìjíríà ni ipari awọn ọdun 1940 o jẹ ọkan ninu awọn oṣere dudu ti o gbajumọ julọ ti ilu gẹẹsi ati ninu ibo ibo kan ti a ṣe ni ọdun 1947 o ṣe atokọ laarin awọn oṣere ayanfẹ 15 ti ilu gẹẹsi ti o...
adimu williams adim williams jẹ oludari fiimu naijiria ti ọ mọ julọ fun iṣẹ rẹ lori abuja connection trilogy ti awọn fiimu</link> ti o nilo itọkasi
akinpelu obisesan akinpelu obisesan 1889 1963 jẹ akọroyin ọmọ orilẹede naijiria oniṣowo ati oloselu o wa laarin ẹgbẹ kan ti awọn ọmọ ile-iwe ti o kọ ẹkọ ni ibérẹ ọrundun ogun ti ọ tọju awọn igbasilẹ ikọkọ ti awọn iṣẹ wọn ati awọn ti ọ tun jẹ agbọrọsọ ni awọn iṣẹlẹ iṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú wọn ni wọ́n tẹ àfihàn wọn jáde nínú...
fredrick kúmókụn adédeji haastrup fredrick kúmókụn adédeji haastrup jé ẹni tí wọ́n bí ní sẹ́ńtúrì kọkàndínlógún sínú ìdílé ọlọ́la ti bilaro ti ìlú iléṣa ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìdílé mérin tí wọ́n ti máa ń yan ẹni tí á máa darí ìlú nígbà náà lára àwọn ìdílé náà ni biládù bilágbayọ biláro and biláyiréré èyí sì ti wà láti ...
best ogedegbe best ogedegbe 3 september 1954 - 28 septempter 2009 ti a mo si anthony best ogedegbe je agbaboolu naijiria o ku eni odun marundinlaadota 55 ni ile iwosan university college nilu ibadan ni ojo kejidinlogbon osu kesan odun 2009 awon itokasi yi ni a kukuru article jọwọ mu yi